audio stringlengths 34 39 | text stringlengths 2 194 | speaker_id stringlengths 5 5 | gender stringclasses 2
values | age_range stringclasses 3
values | duration float64 0.06 37.4 |
|---|---|---|---|---|---|
audio_split/part-0008/sample_82581.wav | Ó fẹ́ ja ilé-ìfowópamọ́ wema lólè. | MXTT9 | male | 30-over | 3.12 |
audio_split/part-0008/sample_84281.wav | Olùkọ́ ni ẹni tí ń kọ́ni nímọ̀. | LNXWF | female | 30-over | 1.98 |
audio_split/part-0000/sample_100532.wav | Ṣo ma fọ aṣọ ẹ pẹ̀lú owó lálẹ́? | DHXFF | male | 30-over | 2.46 |
audio_split/part-0005/sample_56885.wav | Èló ni wó̩n ń ta ìgò E̩ne̩sí báyìí? | EX2CK | female | 18-29 | 2.4 |
audio_split/part-0005/sample_61633.wav | Ọmọ ọ̀gbẹ́ni Délé sọ pé òun fẹ́ láti di awakọ̀-ojú-òfuurufú bí òun bá dàgbà. | MXTT9 | male | 30-over | 7.32 |
audio_split/part-0005/sample_54852.wav | Béèni, sinimá náà wón ní okòó-lé-ní-irínwó-lé-èje náírà. | MXTT9 | male | 30-over | 5.7 |
audio_split/part-0002/sample_32358.wav | Àwọn kan jẹ̀ oníwà ìrẹ̀lẹ̀ tẹ́lẹ̀. | 2WJTR | female | 18-29 | 2.4 |
audio_split/part-0006/sample_64103.wav | Gbé ohùn rẹ̀ lọlẹ̀. | RXQ5P | female | 30-over | 1.68 |
audio_split/part-0001/sample_24114.wav | Tèmi ló ni ìwé dígí obìnrin tó fi sí pálọ̀ yìí | 7TZW9 | male | 18-29 | 3.36 |
audio_split/part-0002/sample_27264.wav | Lọ ṣiṣẹ́ ní oko ilé ìwé ní ọ̀la! | F354Y | male | 30-over | 2.46 |
audio_split/part-0001/sample_18979.wav | Bábà mi mú mi lọ gé igi inú igbó. | PET7A | male | 6-17 | 3.18 |
audio_split/part-0009/sample_97815.wav | Ifẹ ati alejò ti awọn ara ilu Abia jẹ arosọ, ti o jẹ ki awọn alejo ni itara lẹsẹkẹsẹ. | JDOLK | female | 18-29 | 8.34 |
audio_split/part-0001/sample_24500.wav | È ó gbòdò gbé óró làgbégbé yi mò | A5LD3 | female | 6-17 | 2.7 |
audio_split/part-0008/sample_81611.wav | Ìyá Chinwe, Ngozi, sọ pé Nne. | 39965 | male | 30-over | 1.86 |
audio_split/part-0007/sample_74506.wav | Kí ẹ̀rọ ìtúlẹ̀ tó dé, àáké àti dígà ni wọ́n fi n yọ àwọn igi | C0ZXJ | female | 18-29 | 4.56 |
audio_split/part-0001/sample_22186.wav | Owó ọtí kò wọ́n tó bẹ́ẹ̀ lọ́dún mẹ́wàá sẹ́yìn | 4NXF4 | female | 18-29 | 2.64 |
audio_split/part-0009/sample_91420.wav | Mo fẹ́ràn láti máa jẹ àsálà. | ZHR4X | female | 18-29 | 2.4 |
audio_split/part-0005/sample_57082.wav | A yá àwọn kẹ́míkà láti lábù ẹ̀kọ́ ìmọ́ nípa kẹ́míkà | IGXMJ | male | 30-over | 4.08 |
audio_split/part-0002/sample_34566.wav | Njẹ awọn ọmọ ẹgbẹ ti Igbimọ Iṣẹ ọna n gbero eyikeyi awọn ifihan ni oṣu ti n bọ? | HZ67C | female | 18-29 | 6.78 |
audio_split/part-0008/sample_87098.wav | Lọ máa ràn àwọn ọmọ aláìníya lọ́wọ́! Bàbá mi Pàṣẹ. | 22E62 | female | 6-17 | 4.8 |
audio_split/part-0008/sample_86221.wav | Mi ò rò wí pé e̩gbé̩ òkùnkùn ni e̩gbé̩ e̩lé̩mu tí ó wà ní o̩gbà wa | PVCEO | female | 18-29 | 4.5 |
audio_split/part-0001/sample_24355.wav | Owo jẹ ilù ní Ìpínlẹ̀ Òndó ni Nàìjírìà. | 8139X | female | 18-29 | 3.66 |
audio_split/part-0000/sample_14957.wav | Kò sí Log Ride ní Àkúré. | LA0Y9 | female | 18-29 | 2.76 |
audio_split/part-0008/sample_81410.wav | Dín ẹja náà nígbà tí o bá padà dé ilé | H31SQ | female | 18-29 | 3.18 |
audio_split/part-0007/sample_78566.wav | Bàbá mi ni olùdarí ilé-ìwé mi. | K6BEN | male | 6-17 | 2.76 |
audio_split/part-0000/sample_15841.wav | Adarí ń gba wá níyànjú pé kí a máa ṣiṣẹ́ kárakára | MGWAM | female | 18-29 | 3.66 |
audio_split/part-0003/sample_41690.wav | Emi yoo fi caṣeu pataki kan han ọ nigbati mo ba wa ni ọla | VUGDK | female | 30-over | 5.16 |
audio_split/part-0007/sample_72458.wav | Ọ̀rẹ́ mi tó jẹ́ Igbo ni ó kọ́ mi bí wọ́n ti ń se ọbẹ̀ oha | 7TZW9 | male | 18-29 | 4.08 |
audio_split/part-0009/sample_90149.wav | Àwọn rìpọ́tà wá láti wá bèèrè àwọn ǹkan ní àná | L88Q7 | male | 30-over | 2.52 |
audio_split/part-0004/sample_45455.wav | Ẹlẹ́mu á sí shọ́ọ̀bù lọ́la. | 8P4SZ | female | 18-29 | 2.22 |
audio_split/part-0006/sample_71340.wav | Ǹjẹ́ òun ló ra páàkì Ọ̀rìnlélẹ̀ẹ́dẹ́gbèrin | PDK5R | male | 18-29 | 3.3 |
audio_split/part-0002/sample_35235.wav | Bẹ́ẹ̀ni, mo ma di oníṣòwò | 7VUZF | female | 18-29 | 2.16 |
audio_split/part-0004/sample_5256.wav | A le rí àwo-ìwẹ̀ nínú balùwẹ̀. | II8KP | female | 18-29 | 2.16 |
audio_split/part-0000/sample_11701.wav | Ọkùnrin náà ó ja ìjàkadì lọ́la | 59INZ | male | 18-29 | 3.12 |
audio_split/part-0002/sample_30848.wav | Kano duro bi ọkan ninu awọn ilu ọlọrọ itan ni Naijiria, ti a mọ fun ohun-ini atijọ rẹ | 5UWIC | female | 18-29 | 10.14 |
audio_split/part-0008/sample_84857.wav | Ọkùnrin náà gbá ilé ọtí naa | HSOVJ | male | 18-29 | 1.44 |
audio_split/part-0002/sample_3507.wav | Típà ìyẹ̀pẹ̀ mẹ́jọ ni a já lánàá | F76OQ | female | 18-29 | 3.48 |
audio_split/part-0003/sample_3855.wav | Máa lo ògun ibà pẹlú omi. | Q54MY | female | 18-29 | 2.4 |
audio_split/part-0001/sample_24033.wav | Ọpọlọpọ awọn ọkunrin nifẹ bọọlu | 2SCF8 | female | 18-29 | 3.3 |
audio_split/part-0001/sample_17967.wav | Ìwọ́ mọ̀ pé ìṣe olóogun ni Abacha gbé wọ ipò ààrẹ lásìkò rẹ̀? | LZG01 | male | 18-29 | 5.46 |
audio_split/part-0004/sample_53610.wav | Kílódé ti o fí n fowó pa ọmọbìnrin náà lára | U5QAU | female | 18-29 | 2.94 |
audio_split/part-0008/sample_85196.wav | Wọ́n máa lo gétì onírin náà | 3ZVRE | female | 18-29 | 2.88 |
audio_split/part-0002/sample_27542.wav | Ṣo ma fọwọ́sowọ́pọ̀ pẹ̀lú olùdarí rẹ? | SWZ18 | female | 30-over | 2.88 |
audio_split/part-0000/sample_101274.wav | Gbogbo Àlọ́ Yorùbá ló ní Ìjàpá nínú | 6NWZ2 | male | 18-29 | 3.24 |
audio_split/part-0009/sample_926.wav | Àwọn òṣìṣẹ́ kọ́sítọ́ọ̀mù ní àǹfààní láti yẹ gbogbo ẹrù wò. | MXTT9 | male | 30-over | 4.32 |
audio_split/part-0008/sample_8251.wav | Àwọn òṣìṣẹ́ ìjọba kìí lọ sí ibiṣẹ́ ní òpin ọ̀sẹ̀ | KJZZS | female | 30-over | 4.14 |
audio_split/part-0001/sample_19254.wav | Mo n reti awọn iru ẹrọ media awujọ tuntun | CSLLW | male | 6-17 | 4.26 |
audio_split/part-0008/sample_80858.wav | Mo n rà àwọn nkan kan tí mo fẹ́ mú lọ sí ìyà àgbà | O0GW8 | male | 18-29 | 4.2 |
audio_split/part-0006/sample_64335.wav | Olùkọ́ ni àwọn tí wọ́n máa ń kọ́ àwọn ọmọ ní ilé-ìwé | BN1ZC | female | 18-29 | 4.5 |
audio_split/part-0006/sample_66628.wav | Ìlọrin ni mò ń lọ. | CSLLW | male | 6-17 | 1.44 |
audio_split/part-0000/sample_13238.wav | Olè ló sọ Tàfá di èrò ẹ̀wọ̀n | LA0Y9 | female | 18-29 | 2.82 |
audio_split/part-0002/sample_2718.wav | Sá ẹran yíyan yẹn! | 755YF | male | 30-over | 2.64 |
audio_split/part-0008/sample_84270.wav | Koríko dábòbò ọ̀dẹ̀ pẹ̀lú àwọ́ rẹ̀ tò ń dán | DK6N8 | female | 18-29 | 4.92 |
audio_split/part-0007/sample_76678.wav | Awọn baba nla pin ọgbọn wọn ati awọn iriri igbesi aye pẹlu awọn ọmọ-ọmọ wọn | OZCG2 | female | 30-over | 8.4 |
audio_split/part-0002/sample_32708.wav | Ìṣẹ̀dálẹ̀ Èkó Hòtẹ́ẹ́lì wáyé ní 1977. | ZLOOP | male | 18-29 | 3.6 |
audio_split/part-0004/sample_52559.wav | Àwọn Mùsùlùmí máa n lo sí mọ́sálásí ní ojó etì | VLZWS | female | 18-29 | 3.24 |
audio_split/part-0000/sample_17707.wav | Ṣé o tẹtí gbọ ohùn tí oludije náà fẹ́ ṣé? | MAO41 | female | 30-over | 3.42 |
audio_split/part-0002/sample_30272.wav | Àná ni a parí ìpàdé ọdún yii | K0D61 | female | 18-29 | 1.8 |
audio_split/part-0005/sample_56821.wav | Tola ti lọ wón ẹrù rẹ lórí Òṣùwọ̀n. | BVD9K | male | 30-over | 2.34 |
audio_split/part-0006/sample_65862.wav | Ọ̀la ni a ní ìṣẹ́ oko ní oko ilé ìwé. | AYBP6 | female | 30-over | 3 |
audio_split/part-0005/sample_57777.wav | Àṣàkẹ́ fẹ́ràn láti máa rí gbóhùn éégún | ZD9SH | female | 6-17 | 4.14 |
audio_split/part-0006/sample_65858.wav | Ábọ́ọ̀mù Àṣàkẹ́ tí a mọ sí Mr. Money jáde ní ọdún méjì sẹ́yìn. | U6LD6 | male | 18-29 | 5.34 |
audio_split/part-0007/sample_79348.wav | Àwọn ọgbà ẹ̀wọ̀n ààbò yóò gba imọ-ẹrọ tuntun | 8T0JL | female | 18-29 | 3.06 |
audio_split/part-0005/sample_57689.wav | Wọ́n pé àpéjọ gbogbo àdúgbò láti ṣe apero lórí bí ìlú ṣé ń lọ | EAGBK | female | 18-29 | 4.44 |
audio_split/part-0004/sample_50977.wav | James sọ pé ekun náà pa àkùkọ náà | 5ESID | male | 30-over | 2.64 |
audio_split/part-0004/sample_52502.wav | Mo je Sèmó àti ewédú ni ìkómo naa | YH50Q | male | 30-over | 3.36 |
audio_split/part-0005/sample_56054.wav | Mo gbá bọ́ọ̀lù àláfẹsẹ̀gbá. | UPGFZ | male | 18-29 | 2.64 |
audio_split/part-0007/sample_74416.wav | Mo máa kọ ọmọ rẹ̀ ní ilà | Q7FW1 | female | 18-29 | 1.74 |
audio_split/part-0003/sample_36922.wav | béèni Èèrà lọ jé òkú ẹkú yén . | 43FB0 | female | 30-over | 3.42 |
audio_split/part-0001/sample_20395.wav | Akin ṣàjọyọ̀ Kérésìmesì, Ramadan àti ọdún Ọ̀ṣun lọ́dún tó lọ. | SRYA7 | female | 18-29 | 6.36 |
audio_split/part-0009/sample_90252.wav | Sé o lọ sílé bàbá re ni Òsogbo? | YT0T2 | male | 18-29 | 3.18 |
audio_split/part-0006/sample_69540.wav | Kafetéríà jẹ́ irúfé ilé óúnjẹ níbi tí ènìyàn yóò ti mú irú óúnjẹ tí ó fẹ́ jẹ́ | IJ4DB | female | 18-29 | 6.3 |
audio_split/part-0010/sample_99932.wav | Ọgbẹ́ inú máa ń mu ẹnití ọ̀ kí ń jẹun | 4XT0F | female | 18-29 | 2.16 |
audio_split/part-0000/sample_15477.wav | Àwọn obìnrin ń kópa nínú ètùtù tó ní ìtumò | 43FB0 | female | 30-over | 2.94 |
audio_split/part-0001/sample_18072.wav | Ta ló ma lọ sí ayẹyẹ àwọn ẹgbẹ́ eégún ní ìrọ̀lẹ́? | 43FB0 | female | 30-over | 4.26 |
audio_split/part-0007/sample_7780.wav | A driver parked at the road side | 8Q583 | male | 18-29 | 2.52 |
audio_split/part-0001/sample_19921.wav | Ìyá ọkọ Shila burú gan-an. | E9LKY | female | 18-29 | 2.58 |
audio_split/part-0004/sample_52628.wav | Kii ṣe gbogbo idile mi, diẹ ninu wọn ní | HH0CR | female | 18-29 | 3.36 |
audio_split/part-0006/sample_62973.wav | Ilé ìtọjú arọ máa n sábà jìnnà sí ìlú. | QQ7AT | female | 30-over | 3.72 |
audio_split/part-0008/sample_81002.wav | Gbé nu dákẹ́ kí o ṣọ èdè Lárúbáwá! | MJVJE | male | 18-29 | 3.48 |
audio_split/part-0009/sample_92276.wav | Ilé-iṣẹ́ Golden penny ṣe ìpolówó ọjà lánàá | SKWXH | male | 6-17 | 3.12 |
audio_split/part-0006/sample_67739.wav | Àwọn etutu náà yóò parí lọ́dún tó ń bọ̀. | J99KG | male | 18-29 | 3.12 |
audio_split/part-0004/sample_50846.wav | Ṣé wọ́n máa ṣí máàlù náà lọ́la? | OQZCC | male | 18-29 | 2.58 |
audio_split/part-0002/sample_31118.wav | Bọlá tí ṣiṣẹ́ bí Alákóso ilé ọtí yìí rí. | M5C3V | female | 18-29 | 4.2 |
audio_split/part-0007/sample_72220.wav | Àwọn ará Columbia máa ń ṣọ èdè Spanish. | JKPOJ | male | 18-29 | 4.44 |
audio_split/part-0004/sample_49356.wav | Àmá ni ipàdé wàtsáp lòlá | 1W2DQ | male | 18-29 | 1.98 |
audio_split/part-0010/sample_989.wav | Àípẹ́ yìí ni mo ti ọdún eégún dé. | 10GEF | male | 18-29 | 3.12 |
audio_split/part-0001/sample_25066.wav | Bẹ́ẹ̀ni, mo máa nu túrótóòlù náà. | 43FB0 | female | 30-over | 2.4 |
audio_split/part-0007/sample_77013.wav | Ó fi yẹtí méjì sí imú rẹ̀ | V6MKF | female | 18-29 | 2.04 |
audio_split/part-0001/sample_23175.wav | Mo sọ wípé kí o má fi ọwọ́ kan iṣu náà | LTZQW | male | 30-over | 4.2 |
audio_split/part-0004/sample_47722.wav | Wọ́n ti sún ẹjọ́ náà síwájú | V6MKF | female | 18-29 | 1.68 |
audio_split/part-0001/sample_1818.wav | Ẹ̀jẹ̀ náà ni ẹ̀fọn ń mu sanra. | N03J6 | female | 18-29 | 2.28 |
audio_split/part-0008/sample_84370.wav | Owó Karosíìnù yóò lọ sókè ní oṣù tó ń bọ̀ | NSOXE | female | 30-over | 4.08 |
audio_split/part-0004/sample_45259.wav | Àwọn akẹ́kọ̀ọ́ ilé ìwé mi tó ẹgbẹ̀rún le loókànlá lé ní ọ́ta lélọ́ọ̀dúnrún. | S40A2 | male | 30-over | 5.04 |
audio_split/part-0002/sample_29306.wav | Ilé Ìtọ́jú Ọpọlọ wà ní Yaba | XEMXP | female | 30-over | 1.86 |
audio_split/part-0009/sample_94077.wav | A ṣe àbẹ̀wò sí pápákọ̀ ọkọ̀ òfurufú Murtala Mohammed ní ọ̀ṣẹ̀ tó kọjá | KY5I7 | female | 30-over | 5.4 |
audio_split/part-0002/sample_34858.wav | Bẹ́ẹ̀ ni, mò ń lo òlù náà. | 5T8SZ | female | 18-29 | 2.04 |
audio_split/part-0006/sample_68094.wav | Ọlá ni ó dìbò fun Adé. | 4IQD5 | male | 30-over | 1.86 |
audio_split/part-0000/sample_100581.wav | Tobi á pàri gbógbó idánilèkò rè ni ilé èkò ólógún lòdún tó n bò | 2ECGF | female | 6-17 | 5.34 |
audio_split/part-0007/sample_7475.wav | Ẹnikẹ́ni ò gbọ́dọ̀ sọ èdè mìíràn yàtọ̀ sí èdè Yorùbá nínú ilé yìí! | HH0CR | male | 18-29 | 5.94 |
End of preview. Expand in Data Studio
YAML Metadata Warning:empty or missing yaml metadata in repo card
Check out the documentation for more information.
- Downloads last month
- 6