Dataset Viewer
Auto-converted to Parquet Duplicate
text
string
audio
audio
speaker_id
string
age_group
string
domain
string
gender
string
àmọ́ a kì í jẹ́ kí wọ́n darí àwọn ìpinnu tó ṣe gbòógì
YAGT1F1
15-29
AG
female
ó béèrè fún ìrànlọ́wọ́ dípò ìdájọ́ èyí sì jẹ́ kí ìdáhùn mi yí padà
YAGT1F1
15-29
AG
female
ìkòkò ọbẹ̀ àtẹ́ ni wọ́n fi kọ́kọ́ rúbọ sí àwọn baba ńlá wa
YAGT1F1
15-29
AG
female
nítorí náà ni àwọn àlejò ṣe lè pẹ́ dé
YAGT1F1
15-29
AG
female
ó yẹ àwọn àmì ara gbígbóná wò ó sì mọ ìgbà tó yẹ kó pe dókítà pàjáwìrì fún ẹranko
YAGT1F1
15-29
AG
female
àwọn àna wa ń fẹ́ ṣèrànwọ́ àmọ́ a fẹ́ dá ìpinnu wa ṣe
YAGT1F1
15-29
AG
female
wọ́n sọ fún wa pé àìka ìbùnkún àwọn baba ńlá wa sí lè mú kí irè oko má ṣe dáadáa
YAGT1F1
15-29
AG
female
àti pé nísinsìnyí ìròyìn súnkẹrẹ fàkẹrẹ ọkọ ti sọ pé kò sí ọ̀nà kankan tí a tún lè gbà
YAGT1F1
15-29
AG
female
ìdààmú ọkàn àwọn ẹranko máa dín kù tí ibùgbé náà bá mọ́ tóní
YAGT1F1
15-29
AG
female
mo pe ọwọ́ aráyé wá; bí yorùbá bí yorùbá ṣe wí
YAGT1F1
15-29
AG
female
a dáwọ̀ dúró lórí àwọn nǹkan kan tí a forúkọ sí
YAGT1F1
15-29
AG
female
a ti fòfin lélẹ̀ ká tó gbà kí àwọn òbí wa wá gbé lọ́dọ́ wa
YAGT1F1
15-29
AG
female
àwọn àgbà sọ ìtàn nípa ètò ìsọmọlórúkọ tí ó [um] ń ṣe tẹnu ìran [um] dé ìran
YAGT1F1
15-29
AG
female
ó ti mọ ohun tó máa ń fa aápọn fún un
YAGT1F1
15-29
AG
female
láti dín [um] wàhálà kù a pinnu [um] pé a ò ní máa sọ nìpa ìjà wa fún àwọn òbí wa
YAGT1F1
15-29
AG
female
àlàfo tó wà láàárín àwọn ewéko máa ń nípa lórí bí wọ́n
YAGT1F1
15-29
AG
female
ó sì máa dín ewu [um] kí àwọn ẹran tó fún wàrà [um] ní àrùn ọmú kù
YAGT1F1
15-29
AG
female
òrùlé [um] náà gbọ́dọ̀ lè fara da ìjì líle líle
YAGT1F1
15-29
AG
female
ìbẹ̀wò òjijì ló jẹ́ ká a ṣètò àwọn oúnjẹ tí kò wọ́nwó
YAGT1F1
15-29
AG
female
wọ́n pinnu láti ṣe ayẹyẹ tíwọn lọ́tọ̀ láti dènà àríyànjiyàn tí kò nídìí lọ́dún yìí
YAGT1F1
15-29
AG
female
ó dára jù lọ láti gbin èso tòmátì lẹ́yìn òjò díẹ̀
YAGT1F1
15-29
AG
female
fi omi tó mọ́ fọ ojú tàbí awọ ara rẹ fún ìṣẹ́jú mélòó kan
YAGT1F1
15-29
AG
female
ó sì ti mọ bí ó ṣe lè bọ́ lára rẹ̀ ní tútù
YAGT1F1
15-29
AG
female
wọ́n máa pín àwọn èso kọkó láti orí kan sí orí mẹ́rin
YAGT1F1
15-29
AG
female
àwọn ewúrẹ́ máa sińmi dáadá tí wọ́n bá wà nínú ilé tó gbẹ tó sì mọ́ tóní
YAGT1F1
15-29
AG
female
àwọn bọ́ọ̀lù [um] òwú máa bú gbàù [um] nígbà tí wọ́n bá ti dàgbà tán
YAGT1F1
15-29
AG
female
ó ṣàkọsílẹ̀ àkókò pàtó tí àwọn àmì tí ó ń ṣàfihàn àìsàn kí wọ́n lè ṣe àyẹ̀wò nígbà ìbẹ̀wò
YAGT1F1
15-29
AG
female
kí wọ́n sì máa tan àrùn kálẹ̀
YAGT1F1
15-29
AG
female
wọ́n bẹ̀rẹ̀ síní tún okùn ìfọkàntán wọn so nípa pí pààlà àti dí dúró lórí àdéhùn
YAGT1F1
15-29
AG
female
àwọn àlejò ń ṣe àdúrà ìlera àti ìdùnnú [um] fún ọmọ tuntun ní ẹyọ kọ̀ọ̀kan [um]
YAGT1F1
15-29
AG
female
mo ró aṣọ funfun kí n tó lo omi òòsà fún ètùtù fún ètùtù ìkórè
YAGT1F1
15-29
AG
female
a máa ń fi ọ̀rọ̀ tó àwọn òbí wa létí
YAGT1F1
15-29
AG
female
àwọn àṣà ìmọ́tótó bí fífọlé àti mímú ìdọ̀tí kúrò máa dènà àrùn ẹsẹ̀ àti ìṣòro awọ ara
YAGT1F1
15-29
AG
female
a tètè kúrò níbi [?] iṣẹ́ láti lọ síbi ìkómọjáde
YAGT1F1
15-29
AG
female
ó sì ṣe àwọn àyípadà nínú ọ̀nà tó gbà ń tọ́jú aláìsàn náà
YAGT1F1
15-29
AG
female
ìtàn ìdílé àti ìṣepọ̀ àwọn alálẹ̀ náà ni wọ́n fi yan orúkọ ọmọ náà
YAGT1F1
15-29
AG
female
ó sọ ìtàn kan níbi àpèjẹ náà tó sì mú kí ìjíròrò àárín wọn jinlẹ̀ sí i [?]
YAGT1F1
15-29
AG
female
ìmọ́lẹ̀ tó wà nínú ọgbà kọ̀ọ̀kan gbọ́dọ̀ tó láti jẹ́ kí wọ́n lè rí àwọn ewúrẹ́ náà dáadáa lójoojúmọ́
YAGT1F1
15-29
AG
female
ká sì fi sínú yìnyín lẹ́yìn tí wọ́n bá ti kó o
YAGT1F1
15-29
AG
female
ó forúkọ sílẹ̀ fún ìwé ìròyìn kan tí wọ́n máa ń fi ránṣẹ́ sí wa lóṣooṣù
YAGT1F1
15-29
AG
female
mo máa tẹ̀ lé ìsọfúnni tó bá jáde nípa irúgbìn tuntun àti àǹfààní tó wà nínú rẹ̀
YAGT1F1
15-29
AG
female
ayẹyẹ náà kéré ṣùgbọ́n ó kún fún ìṣe dáadáa àti ìṣe pàsípàrọ̀ ìṣe pàsípàrọ̀ àṣà
YAGT1F1
15-29
AG
female
kí wàrà má sì lè dà jáde mọ́
YAGT1F1
15-29
AG
female
mo wá rán ara mi ara mi létí pé látara ìfẹ́ ni àwọn òbí wa fi hùwà
YAGT1F1
15-29
AG
female
ó kaǹ sí ibi ìṣèwádìí ibi iṣẹ́ rẹ̀ fún ìmọ̀ràn lórí àbójútó àwọn àgbàlagbà
YAGT1F1
15-29
AG
female
wọ́n tan orin [um] ìbílẹ̀ gẹ́gẹ́ bí i ara ọ̀kan lára orò ì kí [um] ọmọ káàbọ̀
YAGT1F1
15-29
AG
female
ká tó pín irè oko a kọ́kọ́ fún àwọn baba ńlá wa ní ìpín wọn
YAGT1F1
15-29
AG
female
tó ń jẹ́ kó ní ọkàn balẹ̀ àti kó lè fojúkan dáadáa
YAGT1F1
15-29
AG
female
ó yà wá lẹ́nu pẹ̀lú bí ó ti kó àwọn búlọ́kù léra tó ga dáadáa ju ti àtẹ̀yìnwá lọ
YAGT1F1
15-29
AG
female
ohun kékeré kan tí o ṣe láti gbé oúnjẹ tó fẹ́ràn gan-an ló yí ọ̀sán náà padà
YAGT1F1
15-29
AG
female
[um] wọ́n máa ń ń lo àwọn èèpo [um] ẹ̀pà láti fi se oúnjẹ ní ìgbèríko
YAGT1F1
15-29
AG
female
ó yàn láti dáríji ara rẹ̀ fún àwọn àkókò tí sùúrù rẹ̀ kò bá tó
YAGT1F1
15-29
AG
female
àwọn òbí ṣe ìdákẹ́rọ́rọ̀ fún ìgbà díẹ̀ lórí ọjọ́ iwájú ẹbí wọn
YAGT1F1
15-29
AG
female
ó bá wa palẹ̀mọ́ fún ayẹyẹ bó tilẹ̀ jẹ́ pé kìí tẹ̀lé gbogbo ìlànà ìṣẹ̀ṣe
YAGT1F1
15-29
AG
female
ní àkókò ayẹyẹ náà ó ṣàlàyé nípa yíyan orúkọ ọmọ tó ní ìtumọ̀
YAGT1F1
15-29
AG
female
ó gbádùn bíbójútó òwò rẹ̀ bí ó ti ń bọ̀wọ̀ fún ìfẹ́ ọkọ rẹ̀
YAGT1F1
15-29
AG
female
a ṣàkíyèsí pé ó bẹ̀rẹ̀ síní dá àwọn ohùn àwọn tó súnmọ́ mọ̀ dáadáa lọ́sẹ̀ yìí
YAGT1F1
15-29
AG
female
ẹ̀bùn fún ìsàmì ọdún ákọ́kọ́ ọdún ákọ́kọ́ tí wọn jọ ṣe wà lára ẹ̀bùn oríkádún ùn wọn
YAGT1F1
15-29
AG
female
lẹ́yìn gbogbo ẹ̀ ó bọ́wọ̀ fún ohun tí mo fẹ́ láti gba àyè láti dá ronú
YAGT1F1
15-29
AG
female
líló kóróbá ónírin tí [um] kì [um] kì jẹ́ kó dọ̀tí máa jẹ́ kí wàrà wà nípò tó [um] dára
YAGT1F1
15-29
AG
female
wọ́n ṣàfihàn ara wọn han ẹnì kan tó dá jókòó níbi ìpéjọ àsè oúnjẹ alẹ́
YAGT1F1
15-29
AG
female
ó béèrè fún àkókò láti sàn kí ó tó ṣòrọ̀ nípa ìgbẹkẹ̀lé tí ó já sásán
YAGT1F1
15-29
AG
female
ibi tó mọ́ tóní máa jẹ́ kí ọkàn àwọn àlejò balẹ̀ nípa
YAGT1F1
15-29
AG
female
tàbí [um] tí wọ́n sin ẹran fún ète ìbímọ
YAGT1F1
15-29
AG
female
mo kẹ́kọ̀ọ́ pé tí wọ́n bá tètè bẹ̀rẹ̀ sí fún wàrà
YAGT1F1
15-29
AG
female
wọ́n wá fún oúnjẹ alẹ́ nítorína ni a se wá ilé oúnjẹ tí owó wọn kò pọ̀jù
YAGT1F1
15-29
AG
female
wọ́n lọ wo yíká [um] ilé ìtọ́jú àwọn àgbàlagbà kan tí ọ̀rẹ́ ìdílé wọn kan dámọ̀ràn [um] pé kí wọ́n lọ
YAGT1F1
15-29
AG
female
a ma ń pín àkokò [um] ọdún láàárín àwon òbí wa láì ni [um] ara wa lára
YAGT1F1
15-29
AG
female
ó gba àwọn àdàkọ ìtòlẹ́sẹẹsẹ láti tọ pinpin àwọn oògùn àti ìmúrasílẹ̀ fún ìbátan rẹ̀
YAGT1F1
15-29
AG
female
ó rán gbogbo ènìyàn létí láti fèsì kí ó tó di ìparí kíkà orí kọ̀ọ̀kan tó gbẹ̀yìn
YAGT1F1
15-29
AG
female
ọmọ ẹ̀gbọ́n mi wò bí wọ́n ti ń ṣe ìwẹ̀nùmọ́ ó sì ń kọ nípa ìṣẹ̀ṣe
YAGT1F1
15-29
AG
female
ó pàpà dárí [um] jì í ṣùgbọ́n ó béèrè fún ìgbésẹ̀ díẹ̀díẹ̀ fún [um] ìpadàbọ̀sípò wọn
YAGT1F1
15-29
AG
female
kí ó sì ní ìmúbọ̀sípò ní àgọ́ ara rẹ̀
YAGT1F1
15-29
AG
female
ó lè bà jẹ́ kó sì máa rùn
YAGT1F1
15-29
AG
female
a lo àkànṣe ìgbálẹ̀ kan láti gbá ilẹ̀ òòsà ká tó rúbọ
YAGT1F1
15-29
AG
female
wọ́n fi ìwé ìfipè ránṣé fún àpéjọ [um] òpin ọ̀sẹ̀ láti kí ọmọ tuntun wọn káàbọ̀ sáyé [um]
YAGT1F1
15-29
AG
female
lílo àwọn ọ̀já onírin tí wọ́n fi irin ṣe máa ń jẹ́ kí afẹ́fẹ́ máa wọlé dáadáa
YAGT1F1
15-29
AG
female
wọ́n ṣètò àpéjọ kékeré láti ṣe àjọyọ̀ àlékún tó dé bá ìdílé wọn
YAGT1F1
15-29
AG
female
ó túbọ̀ kó àwọn páàdì àti àpò tí wọ́n fi ń kó ìdọ̀tí nítorí tí jàǹbá bá ṣẹlẹ̀ lójú ọ̀nà
YAGT1F1
15-29
AG
female
tí ó bá rí àmi àápọn bẹ̀rẹ̀ sí í farahàn
YAGT1F1
15-29
AG
female
mo kẹ́kọ̀ọ́ pé ìgbà tá a bá sinmi díẹ̀ pàápàá lè mú kí ọkàn wa balẹ̀
YAGT1F1
15-29
AG
female
dádì sọ pé tí wọ́n bá fi àyè tó yẹ sáàárín àwọn igi náà
YAGT1F1
15-29
AG
female
[um] ijó àti ìlù ló tẹ̀lé ètùtù [um] àkọkọ fún ìkórè
YAGT1F1
15-29
AG
female
a ká bí ó ti ń ròjọ́ pẹ̀lú ìdùnnú nígbà tó ń ṣeré pẹ̀lú àwọn ohun ìṣeré rẹ̀ lórí rúújì
YAGT1F1
15-29
AG
female
ìbátan [?] wa fí tùràrí yíká [um] apẹ̀rẹ̀ ìkórè náà
YAGT1F1
15-29
AG
female
ìtọọrọ ìdáríjì ṣòro ṣùgbọ́n ó ṣe kókó [um] láti tún okùn ìbásepọ̀ tó [um] ti ń bàjẹ́ ṣe
YAGT1F1
15-29
AG
female
ìfẹ́ wọ́n nínú oúnjẹ ló jẹ́ kí àárín wọn tún gún lẹ́yìn èdè àìyedè tó wáyé lópin ọ̀sẹ̀ tó kọjá
YAGT1F1
15-29
AG
female
àwọn ẹran tó lágbára máa jẹ́ kí oko wọn dúró sán kí àwọn aráàlú sì fọkàn tán wọn
YAGT1F1
15-29
AG
female
láti dín ìbànújẹ kù àti láti mú ìfarabalẹ̀ rẹ̀ dára síi
YAGT1F1
15-29
AG
female
kí irúgbìn náà tó lè hù dáadáa ó gbọ́dọ̀ jìn tó bẹ́ẹ̀ gẹ́ẹ́
YAGT1F1
15-29
AG
female
kó jẹ́ kí wọ́n wà ní mímọ́ tóní
YAGT1F1
15-29
AG
female
fífọ àtíbàbà ewúrẹ́ láràárọ̀ jẹ́ ara ohun tá a máa ṣe lójoojúmọ́ nínú oko wa
YAGT1F1
15-29
AG
female
ó kíyè sí i pé ẹnì kan ń ṣàníyàn nípa ọ̀nà tó yẹ kó gbà
YAGT1F1
15-29
AG
female
wọ́n máa ń dìgbà bójú tó ilé kí wọ́n lè pọkànpọ̀ lórí ìdàgbàsókè ara wọn
YAGT1F1
15-29
AG
female
iná òòṣà gbudọ̀ wà ní títàn ní gbogbo òru ọjọ́ orò ìkórè
YAGT1F1
15-29
AG
female
ó yẹ kí [um] wọ́n bẹ̀rẹ̀ sí gbin irúgbìn náà ní kùtùkùtù òwúrọ̀ nígbà tí oòrùn ko mú [um] gan
YAGT1F1
15-29
AG
female
wọ́n tètè ṣètò àyẹ̀wò láti lè yẹra fún súkẹrẹfà kẹrẹkọ̀ àti láti dín ìdààmú ẹran ọ̀sìn náà kù
YAGT1F1
15-29
AG
female
má ṣe fi ọwọ́ tó ti dọ̀tí fọ ojú nígbà tó o bá ń ṣiṣẹ́ lóko
YAGT1F1
15-29
AG
female
[um] mo kẹ́kọ̀ọ́ pé ìdààmú ọkàn [um] máa mú kí wàrà má dà dáadáa ó sì máa mú kí wàrà dín kù
YAGT1F1
15-29
AG
female
wọ́n sọ àwọn àbá ìjáde tí wọ́n lè lè ní tí kò wọ́n tí gbogbo èèyàn sì máa gbádùn
YAGT1F1
15-29
AG
female
End of preview. Expand in Data Studio

African Voices Dataset

Multi-speaker voice dataset for African languages.

Yoruba

Audio + transcript pairs organized by speaker, with age_group, domain, and gender metadata.

Downloads last month
324