instruction stringlengths 10 114 | input stringclasses 1
value | output stringlengths 100 15.6k |
|---|---|---|
Sọ fún mi nípa Belete Molla. | Belete Molla (Amharic: በለጠ ሞላ) jẹ́ olóṣèlú ará Ethiopia tí wọ́n yàn sípò Minisita fún Ĩmótuntun àti Ìmọ̀ ẹrọ ní ọdún 2021, ó sì tún jẹ́ olùdásílẹ̀ àti Alága ẹgbẹ́ òṣèlú apá ọ̀tún Amhara tó ń jẹ́ National Movement of Amhara (NaMA), ẹgbẹ́ olóṣèlú aṣàájú ilẹ̀ Amhara ní Ethiopia.. | |
Fi Phoeby Okech hàn mí. | Phoeby Okech jẹ agbabọọlu lobinrin órilẹ ede kenya ti a bini 10, óṣu October ni ọdun 1994. Agbabọọlu naa ṣere fun Vihiga Queens FC gẹgẹ̀bi Midfielder. | |
Kí ló wà ní ìtàn Igbesiaye Baṣọ̀run Gáà nípa Baṣọ̀run Gáà? | Sugbọn iku Basọrun Gaa se akoba nla fun ijọba Ọyọ akọkọ, tori lẹyin iku Gaa ni ẹdinku ba bi awọn ọmọ ogun rẹ ti dangajia si ati agbara ilu naa, tawọn ilu kan si n sa kuro labẹ rẹ, titi ti Ọyọ ile akọkọ fi tu lọdun 1836. | |
Kí ni àwọn ohun pàtàkì nípa Barack Obama? | Barack Hussein Obama Jr. (ojó-ìbí rẹ̀ ni ọjọ́ kẹrin oṣù kẹjọ ọdún 1961) jẹ́ olóṣèlú ará Amẹ́ríkà tí ó ṣiṣẹ́ gẹ́gẹ́ bí ààrẹ kẹrinlélógójì ti Amẹ́ríkà láti ọdún 2009 sí ọdún 2017. Gẹ́gẹ́ bí ọmọ ẹgbẹ́ òṣèlú òṣèlú Democrat, ó jẹ́ ààrẹ ọmọ ilẹ̀ Áfíríkà Amẹ́ríkà àkọ́kọ́. Obama ti ṣiṣẹ́ gẹ́gẹ́ bí sẹ́nẹ́tọ̀ Amẹ́ríkà tí ó ṣojú ... | |
Jọ̀wọ́ sọ nípa Àwọn àmì-ẹyẹ tí ó gbà ti Pius Adesanmi. | Ní 2001, Ìwé Adesanmi's àkọ́kọ́ The Wayfarer and Other Poems, gba àmì ẹ̀yẹ ewì Ẹgbẹ́ àwọn Òǹkọ̀wé Orílẹ̀èdè Nàìjíríà (Association of Nigerian Authors' Poetry Prize). | |
Kí ni Ẹ̀sìn Yorùbá nípa Aganju? | Ní àwọn àgbègbè kan nílé Yorùbá ni orílẹ̀ èdè Nàìjíríà àti orílè èdè Bìnì, Aganju jẹ́ Òóṣà tí ó fi ìgbà jẹ́ Ológun àti Ọba láti ìlú Sakí, tí ó wà ní Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ lóde Òní nílé Nàìjíríà. Wọ́n gbà pé ó máa ń rìn pẹ̀lú Idà lọ́wọ́ àti pé ó máa ń jà pẹ̀lú Iná èyí tí ó jé pé ó fé jó tí Ṣàǹgó tí ó máa ń rán Àrá àti Mònàmóná ... | |
Kí ló wà ní Iṣẹ́ rẹ̀ nínú ara nípa Ṣúgà? | Ṣúgà jíjẹ bẹ̀rẹ̀ ní inú ọdún 20th century, àmọ́ ṣá, àwọn oníwádí ìmọ̀ ìjìnlẹ̀ wá ń ṣe ìwádí ìyàtọ̀ tó wà láàrín jíjẹ ṣúgà lásán àti àwọn súgà tí wọ́n ti tún ṣe agbélẹ̀rọ rẹ̀ kò léwu fún ìlera ọmọnìyàn. Wọ́n wá fìdí rẹ̀ múlẹ̀ wípé àpọ̀jù ṣúgà jíjẹ ní ìpalára tó lágbára fún ìṣẹ̀mí ọmọnìyàn nítorí wípé ó lè fa àwọn àìsàn ... | |
Kí ni àwọn ohun pàtàkì nípa Lille? | Lille (ìpè Faransé: [lil]Àdàkọ:IPA audio link; Duki: Rijsel) jẹ́ ìlú kan ní apá àríwá Fránsì. == Itokasi == | |
Kí ni àwọn ohun pàtàkì nípa Carol Moseley Braun? | Carol Elizabeth Moseley Braun (ojoibi August 16, 1947) je ara Amerika asetobinrin, oloselu ati agbejoro to soju fun ipinle Illinois ni Ile Alagba Amerika lati 1993 de 1999. == Itokasi == | |
Ṣàlàyé ohun tí 1 E11 m² jẹ́. | To help compare orders of magnitude of different geographical regions we list here surface areas between 100,000 km2 and 1,000,000 km2. See also areas of other orders of magnitude. Areas smaller than 100,000 km2 100,000 km2 is equal to: 1 E+11 m2 38,600 square miles a square with side 316 km a circle with radius 178 km... | |
Ṣe àlàyé Awọn atẹjade fún Adeyinka Abideen Aderinto. | Pathways and Motivations for Cyber Fraud Involvement among Female Undergraduates of Selected Universities in South-West Nigeria | |
Kí ni Iṣẹ Emmanuel ati Àṣèyọri nípa Emmanuel Botwe? | Botwe pẹlu awọn akẹgbẹrẹ Andrews Ebenezer, Daniel Doe, Jennifer Abitty, Grace Atipaka ati Eryram Yaa Migbodzi kopa ninu idije agbaye lori Badminton fun igba akọkọ. | |
Kí ni Events nípa 4 March? | 1681 - Charles II of England grants a land charter to William Penn for the area that will later become Pennsylvania. | |
Ṣàlàyé Sise oso re nínú National Arts Theatre. | Awon Kongila ara ile Bulgaria ni won ba orile ede Naijiria ko gbangan naa ti won si dara si ti o fi fe jo Palace of Culture and Sports ti ile Varna, ni ilu Bulgaria ( 1968), Amo gbogan National Arts Theatre ti ilu Eko tobi ju afara pe yi lo. | |
Sọ fún mi nípa Awọn atẹjade akiyesi ti Ismail El Gizouli. | Ifowoleri, Owo-ori ati Inawo ti Awọn ile-iṣẹ Abala Agbara ni Sudan, Iṣẹ Agbara Afirika, Banki Idagbasoke Afirika, 1994 | |
Sọ fún mi nípa Ìdọ̀tí ti Ilorin. | Ìpalára tó le yọ lára ni pé bí wọ́n kò bá yọ àpọ̀ ìdọ̀tí náà ní kíákíá, àìlera àti àrùn le wọ̀pọ̀, torí pé àwọn àpò ìdọ̀tí tí a fi sí lẹ́gbẹ̀ẹ́ ojú pópó wọ̀pọ̀, wọ́n sì bẹ̀rẹ̀ sí í tú ìtànkálẹ̀ ọ́tẹ̀ tó ń yọ̀, tó ń fa ìbànújẹ̀ àti ìnira bá àwọn aráàlú. | |
Kí ni ìtumọ̀ Yvonne Orji? | Yvonne Anuli Orji (bíi ni ọjọ́ kejì oṣù kejìlá ọdún 1983) jẹ́ òṣèré ni orílẹ̀ èdè Nàìjíríà àti Amẹ́ríkà. Ó gbajúmọ̀ fún ipá tí ó kó nínú eré Insecure ní ọdún 2016, èyí tí ó jé kí wọn yàán fún àmì ẹ̀yẹ tí Primetime Emmy Award àti NAACP Image Awards. | |
Ṣàlàyé Òsèlú nínú Peter Obi. | Ni osù karun 2007, Peter Obi tún fi ipò Gomina sílè léyìn tí Andy Uba wolé gegebi Gomina ìpínlè Anambra, o tori oro yìí lo ilé ejo lekansi, o ni sáà ijoba rè to ye kó bèrè bi odun 2003 kí o sì pari ni odún 2007 bèrè ní odun 2006, nitori náà, kí ilé ejó jé kí sáà ìjoba rè di odún 2010(kí ó ba le lo odún merin ìjoba rè p... | |
Kí ló wà ní Oju-iwe Keji nípa Atúmọ̀-Èdè (Gẹ̀ẹ́sì-Yorùbá): E? | equal: v; (Nobody else can equal him in ability.) bá dógba; bá mu kò tún sí eni tó lè bá a dógna ni lilágbara àtise. | |
Ṣe àlàyé Apejuwe fún Parkview Estate, Ikoyi. | Ohun-ini naa tun gbalejo ọpọlọpọ awọn ile itura bii Ibugbe Ile-ẹjọ Pearl & Awọn ile itura, Upperclass Suites ati ọpọlọpọ awọn miiran. | |
Kí ni ìtumọ̀ Àtòjọ àwọn àgbègbè tí wọ́n yà sọ́tọ̀ fún ètò ìkànìyàn ní ìpínlẹ̀ Alabama? | Àwọn ibi ìyàsọ́tọ̀ fún ètò ìkànìyàn jẹ́ àwọn àgbègbè tí Ìjọba kò ì tí ì mú mọ́ra, tí wọ́n kò sìn ní asojú adìbòyàn àti àlà lábẹ́ òfin Àpapọ̀ àwọn [[Census-ibi ìyà sọ́tọ̀ fún ètò ìkànìyàn ní ìpínlẹ̀ Alabama jẹ́ énìdínlógúnlélọ́gọ́rùn ún (118) Semmes- Mobile County *2013 | |
Ṣàlàyé Isẹ́ orin nínú Ilerioluwa Oladimeji Aloba (Mohbad). | Àwo orin "Blessed" ní ó kọ́ ṣe ní June 2023, lẹ́hin tí o kúro lábẹ ilé iṣẹ́ Marlian Records tí o ṣẹda ilé iṣẹ́ orin tirẹ̀ tí ó pè ni "Imolenization". Blessed jẹ́ àkójọpọ̀ orin ọtọtọ mẹjó tí wọ́n gba ogun-isẹju lapapo. lara wọn ni o ti kopa pẹlu Zlatan àti Bella Shmurda, labẹ ìsàkóso Niphkeys ati Timi Jay. Àwo naa gbégb... | |
Kí ni àwọn ohun pàtàkì nípa São Tomé? | São Tomé (olugbe 56,166 ni 2005) ni oluilu orile-ede São Tomé ati Príncipe be sini ohun ni ilu totobijulo nibe. Oruko re wa lati ede Portugi fun Apostoli "Thomas Mimo". == Itokasi == | |
Kí ni Aldehyde dehydrogenase 9 family, member A1? | 4-trimethylaminobutyraldehyde dehydrogenase jẹ́ enzyme nínú ara àwọn ènìyàn tí ALDH9A1 gene máa ń kóòdù fún. | |
Kí ni àwọn ohun pàtàkì nípa Peace Uzoamaka Nnaji? | Peace Uzoamaka Nnaji (ojoibi 28 December 1952 ni Ipinle Enugu ) jẹ olóṣèlú ọmọ orilẹ-ede Nàìjíríà . Wọ́n kọ́kọ́ yàn án lábé ẹgbẹ́ òṣèlú People’s Democratic Party lọ́dún 2007, wò tún dibo yàn lẹ́ẹ̀kejì ní ọdún 2011 ní Ilé Ìgbìmọ̀ Aṣòfin Nàìjíríà . | |
Kí ló yẹ kí n mọ̀ nípa Mojeed Fatai Adebola? | Mojeed Fatai Adebola j olóṣèlú ọmọ orílè-èdè Nàìjíríà. Lọwọlọwọ o n ṣiṣẹ gẹgẹbi aṣoju ipinlẹ ti o n ṣojú àgbègbè Ibeju Lekki I ni ile igbimọ aṣofin ìpínlè Eko. Ni ọjọ́ 13 oṣù kìíní ọdún 2024, won dibo yán gẹ́gẹ́bíi igbá-kejì Ààrẹ ile igbimo aṣòfin ìpínlè Èkó, lẹ́yìn ti wọn ti yọ olórí ile ìgbìmọ̀ aṣòfin, Mudashiru Obas... | |
Ṣe àlàyé Ìgbésí ayé ìbẹ̀rẹ̀ fún Femi Otedola. | Wọ́n bí Otedola ní ìlú Ìbàdàn, olú ìlú ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́, gúúsù ìwọ̀ oòrùn Nàìjíríà, nínú ìdílé olóògbé Sir Michael Otedola, Gómìnà Ìpínlẹ̀ Èkó láti 1992 sí 1993. Arakunrin Femi Otedola se igbeyawo pelu Nana Otedola, Ile Iwe Obafemi Awolowo University ni o ti jade leyin eyi to bere si ni mojuto ise ite iwe baba re, to si j... | |
Kí ni ìtumọ̀ Anup Singh Choudry? | Anup Singh Choudry (ti a bi 13 August 1949), jẹ agbẹjọro ara ilu Uganda kan, idajọ ati onkọwe ti o ṣe idajọ ododo ti Ile-ẹjọ giga ti Uganda lati 2 May 2008 titi di 11 Oṣu Kẹjọ ọdun 2014. O ti bura ni ibi ayẹyẹ kan ni Ile Ijọba ni Entebbe niwaju Alakoso Yoweri Museveni ati Adajọ agba Benjamin Odoki. Oun ni Sikh akọkọ at... | |
Ṣàlàyé Igbesiaye nínú Aisha Augie-Kuta. | Augie-Kuta ni oloselu obinrin akọkọ lati dije fun ile aṣaaju-ọna awọn aṣaaju labẹ ẹgbẹ nla kan fun Argungu-Augie Federal Constituency ni Ipinle Kebbi, Nigeria. Augie-Kuta jẹ oluranlọwọ igbagbogbo ni apejọ ọdọọdun ti awọn oluyaworan, Apewo fọtoyiya Nigeria & Apejọ; igbimọ ati agbọrọsọ ni ọpọlọpọ awọn iṣẹlẹ; ati pe o ti ... | |
Kí ni Ijọba ti Benin nípa Igba atijọ? | Ijọba Benin jọba lati c.1200 - 1897 ni eyi ti o wa ni gusu Naijiria bayi. Ilu Benin jẹ ijọba ọlọrọ ti o to eniyan miliọnu meji. Wọ́n ń tẹ̀ lé ìsìn ìbílẹ̀ Áfíríkà tí a mọ̀ sí Edo, èyí tí ọ̀pọ̀lọpọ̀ ènìyàn ní Nàìjíríà ṣì ń ṣe lónìí. | |
Ṣe àlàyé Ìgbéjáde fún Omo Ghetto: The Saga. | Akindele sọ ọ di mímọ̀ pé kí wọ́n tó bẹ̀rẹ̀ apá kejì fíìmù yìí ní oṣù kejì ọdún 2020, òun ṣe àgbéjáde àwọn àwòrán rẹ̀ àtijọ́ tó yà pẹ̀lú Eniola Badmus. Àwòrán yíyà fún fíìmù náà bẹ̀rẹ̀ ní oṣù February, ọdún 2020. Ètò fíìmù yìí náà tún jẹ́ ìbẹ̀ẹ̀rẹ̀ ìpọwọ́ṣiṣẹ́ pọ̀ òun àti ọkọ rẹ̀ JJC Skillz, gẹ́gé bí olùdarí fíìmù náà.... | |
Kí ló wà ní Àṣà nípa Ilorin? | Ìpinnu láti tún masálàsi àárín Ìlórin ṣe bẹrẹ ní ọdún 2007, nígbà tí Alhaji Ibrahim Zulu Gambari, CFR, Emir kẹtàlá Ìlórin, pẹlú ìrànlọwọ Abubakar Bukola Saraki, Turaki Ìlórin àti Gómìnà ṣáájú ìpínlẹ Kwara, dá ẹgbẹ ìmúlò àgbékà yìí sílẹ, tí Alhaji Shehu Abdul-Gafar darí. | |
Ṣe àlàyé Bó ba tó Àsìkò Àtisu, Fúrọ̀ níláti lá fún Ìlú ẹ̀yọ. | Bàbá Amòye wò mi. Ó fẹ̀rín sí. Bàbá Amòye tún ń bá ọ̀rọ̀ rẹ lọ pé: Méjì là á wònìyàn; Bí ò jẹ́ ti yínyìn, a jẹ́ ti èébú. Gbogbo ẹyẹ kọ́ ló sì ṣe ń sùn lálẹ́. Gbogbo ìgbà tí ẹ̀nìyàn bá wọsọ olúmẹ̀yẹ kọ́ laráyé máa ń fẹ́ kọ́ yẹni. Àrokò ńlá ni ọmọ tó bẹ́tọ́ sí ọ lára pa fún ọ ti o ò mọ̀. Kò mọ̀ ṣéni tó le ríre tí ò ni ri... | |
Fi Àfijẹ́rìí hàn mí nínú Ìdíje afigi gbá láàrin apẹ̀rẹ̀ ní Olimpiiki Ìgbà ooru 2020 – Àwọn ọkùnrin.. | èto ìpele ìkópa ìdíje bọ́ọ̀lù aláfigigbá láàrin apẹ̀rẹ̀ láti rí i dájú pé àwọn ọkùnrin mẹ́rìndínláàdọ̀rún àti Obìnrin mẹ́rìndínláàdọ̀rún gba ààyè ìkópa; ìwọ̀n pápá àwọn ọkùnrin tí kò ní àmì-ẹ̀yẹ kan náà ń yí padà láti dé ibi-àfojúsùn yẹn. Lẹ́yìn àtúnṣe nítorí àjàkálẹ̀-àrùn COVID-19, àwọn àkókò ìpele náà ni a yàn láti ọ... | |
Kí ni àwọn ohun pàtàkì nípa 19 July? | Ọjọ́ 19 Oṣù Keje tabi 19 July jẹ́ ọjọ́ 200k nínú ọdún (201k ní ọdún tódọ́gba) nínú kàlẹ́ndà Gregory. Ó ṣẹ́ ku ọjọ́ 165 títí di òpin ọdún. | |
Kí ló yẹ kí n mọ̀ nípa Francis Bacon? | Francis Bacon, 1st Viscount Saint Alban, KC (22 January 1561 – 9 April 1626) je amoye, agbaalu, onimo sayensi, agbejoro, adajo ati olukowe ara Ilegeesi. == Itokasi == | |
Kí ni ìtumọ̀ Bodija? | Bódìjà ni àdúgbò kan ní ìlúÌbàdàn, ní ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́. Àdúgbò yí di gbajú gbajà pẹ̀lú ilé ìgbé alákọ̀ọ́pọ̀ tí wọ́n kọ́ síbẹ̀ láàrín ìgboro ìlúìbàdàn lẹ́yìn ìgbòmìnira ilẹ̀ Nàìjíríà ní ọdún 1960. Irúfẹ́ ilé ìgbé méjì ni ó wà ní àdúgbò náà, àkọ́kọ́ ni bódìjà ayé àtijọ́ àti bódìjà tìgbàlódé, bẹ́è sì ni ó tún jẹ́ ilé ìgbé fú... | |
Jọ̀wọ́ sọ nípa 17 July. | Ọjọ́ 17 Oṣù Keje tabi 17 July jẹ́ ọjọ́ 198k nínú ọdún (199k ní ọdún tódọ́gba) nínú kàlẹ́ndà Gregory. Ó ṣẹ́ ku ọjọ́ 167 títí di òpin ọdún. | |
Ṣe àlàyé Iṣẹ́ rẹ̀ fún Betty Acquah. | Acquah ti ń ṣiṣẹ́ fún ọdún méje ní yàrá àwọn àwòrán fún Center for National Culture ní ìlú Accra, ó sì ti ń ṣàfihàn àwọn iṣẹ́ rè ní Berj Art Gallery láti ọdún 2002 wọ 2005. Ó jẹ́ ọmọ-ẹgbẹ́ Ghana Association of Visual Artists. Ní oṣù kẹfà ọdún 2019, ó sọ ọ́ di mímọ̀ nínú ìfọ̀rọ̀wánilẹ́nuwò kan tí Newsday BBC ṣe fún un p... | |
Ṣe àlàyé Iṣẹ́ fún Zara Mohamed. | Ó bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ mọ́dẹ́lì nígbà tí ó wà ní ilé ẹ̀kọ́ gíga. Ó ti ṣe mọ́dẹ́lì fún Halston, Gianni Versace, Calvin Klein, Issey Miyake and Donna Karan. àti Tess Management. Iman bẹ̀rẹ̀ sí ní ta jìgì ojú fún àwọn obìnrin ní ọdún 1994. Ní ọdún 2012, ó fi Ayaan àti Idyl Mohalim fi ṣe àmbásẹ́dọ̀ fún ilé iṣẹ́ rẹ̀. Iman kópa nínú ... | |
Kí ló wà ní Ife Empire nípa Ìtàn àwọn Yorùbá? | Àṣà àtọwódówó yii ṣe déédéé pẹ̀lú ipa Ilé-Ifè gẹgẹbi ibùdó ìṣòwò pàtàkì. Àyè ti Ijọba Ifè wa jẹ ki ikopa rẹ pọ si ni awọn nẹtiwọọki ìṣòwò ọpòlọpò tí o wà ní Ìwọ̀-Oòrùn Áfíríkà. Lara àfiyèsíni ẹ̀rí ilé iṣẹ́ ìlẹ̀kẹ̀ gíláàsì kan tí ó wà ní Ilé-Ifẹ̀. Awọn onítàn ìwádìí ilẹ̀ | |
Jọ̀wọ́ sọ nípa Ìgbésí ayé rẹ̀ ti Rozena Maart. | District Six ní ìlú Cape Town, ní South Africa ni wọ́n bi sí. Wọ́n fi ipá lé ẹbí rẹ̀ kúrò ní District Six ní ọdún 1973 látàri àṣẹ ìjọba ti ọdún 1987. Nígbà tí ó wà ní ọmọdún mẹ́rìnlélógún (24), wọ́n yàn án fún àmì-ẹ̀yẹ "Woman of the Year" tí wọ́n ṣe ní Johannesburg, fún iṣẹ́ rè lórí títako ìwà ipá sí àwọn obìnrin, àti ... | |
Kí ni àwọn ohun pàtàkì nípa Zara Mohamed? | Zara Mohammed Abdulmajid (bíi ni ọjọ́ kẹẹdọgbọn oṣù keje ọdún 1995) jẹ́ òṣèré, mọ́dẹ́lì àti oníṣòwò lórílẹ̀-èdè Uganda. | |
Jọ̀wọ́ sọ nípa Oju-iwe Keji ti Atúmọ̀-Èdè (Gẹ̀ẹ́sì-Yorùbá): E. | gbà à ni mòran pé kí ó máa se idáraya dáadáa. Ìlo. Ìtàn náà se àfihàn tí ó je mó ìlò ìwoye. Isé síse: Olùko náà fún àwon akékòó rè ní isé síse. | |
Sọ fún mi nípa Ìgbìyanjú rẹ̀ láti kọjá gbèdéke Guiness Record ti Hilda Baci. | Àwọn òtòkùlú ènìyàn ní Nàìjíríà ni ó ti kàn sí Hilda láti ìgbà tí ó ti bẹ̀rẹ̀ iná dídá, àwọn bi: Gómìnà Ìpínlẹ̀ Èkó, Babajide Sanwo-Olu; Olùṣọ́ àgùntàn àgbà ti ìjọ Harvester International, Bolaji Idowu; àti olórin Tiwa Savage. | |
Kí ni àwọn ohun pàtàkì nípa Àṣà ilẹ̀ Áfríkà? | Àsà ilẹ̀ Áfríkà pọ̀ loriṣiriṣi , tí ò sí ni idapọ awọn orilẹ-ede pẹlu ọpọlọpọ awọn ẹya ti ọkọọkan ni ihuwasi alailẹgbẹ wọn lati orílẹ̀ Afirika . O jẹ esìn àwọn onírúurú ènìyàn ti o ngbe ni orílè Afirika ati awọn ara ilu Afirika . Ní àkótán, Àsà ní akojọpọ awọn agbara iyasọtọ ti o jẹ ti ẹgbẹ kan ti eniyan kan. Lára àwọn... | |
Ṣe àlàyé Àṣẹ ilé ẹjọ́ náà fún Ilé-ẹjọ́ kòtẹ́milọ́rùn. | ti òfin orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tí wọ́n ṣe àgbéyẹwò rẹ̀ ní ọdún 1999 láti gbẹ́jọ́ àwọn ilé-ẹjọ́ kékèké bíi: | |
Sọ fún mi nípa Bilkisu Labaran. | Bilkisu Labaran jẹ́ oníròyìn ní orílẹ̀-èdè Naijiria òun sì ni olórí èka ilé-iṣẹ́ BBC lórí ìròyìn àti nkan tí ó ń ṣẹlẹ̀ ni Afrika. Ó kópa púpò nínú ìdá BBC pidgin òun sì ni oootu àkọ́kọ́ fún BBC pidgin. Ó wà lára àwọn alamojuto BBC Africa Eye documentaries Kí ó tó dára pò mọ́ BBC, ó jé olùkọ́ ní Yunifásítì Àmọ́dù Béllò,... | |
Kí ni àwọn ohun pàtàkì nípa Abubakar Tafawa Balewa? | Abubakar Tafawa Balewa (December 1912 – January 15, 1966) jẹ́ ọmọ orílẹ̀ èdè e Nàìjíríà, láti apá àríwá ilẹ̀ Nàìjíríà. Balewa jẹ́ Alákòóso Agba (prime minister) àkọ́kọ́ fún ilẹ̀ Nàìjíríà ní ìgbà òṣèlú àkọ́kọ́ ilẹ̀ Nàìjíríà lẹ́yìn ìgbà tí Nàìjíríà gba òmìnira ní ọdún-un 1960. Ẹni àyẹ́sí ni kárí ayé, ó gba ọ̀wọ̀ ní orílẹ... | |
Ṣe àlàyé Iṣẹ fún Ademola Adesina. | Ṣaaju ki o to ṣẹda Rensource, Adesina ṣiṣẹ bi Onisowo ni Ibugbe ni Capricorn Investment Group ni Palo Alto, apa idoko-owo ti Jeff Skoll ati Skoll Foundation. O tun ṣe ipo kan ni Aquifer, ile-iṣẹ idoko-owo ni Ilu Lọndọnu ti o ni nkan ṣe pẹlu Lord Sainsbury ati Gatsby Trust, nibiti o ṣe itọsọna ilana ati idagbasoke iṣowo... | |
Jọ̀wọ́ sọ nípa Curaçao. | Curaçao (pípè /ˈkjʊərəsaʊ/; Duki: Curaçao, Papiamentu: Kòrsou) je erekusu ni apaguusu Omi-okun Karibeani, nitosi etiomi Venezuela. Erekusu Ileagbegbe Curaçao (Dutch: Eilandgebied Curaçao, Papiamentu: Teritorio Insular di Kòrsou), to lamupo mo erekusu gbangba na ati ereku Klein Curaçao ("Curaçao Kekere"), je ikan ninu a... | |
Jọ̀wọ́ sọ nípa Hans Morgenthau. | Hans Joachim Morgenthau (February 17, 1904 – July 19, 1980) je omo Germany ara Amerika] to je ikan ninu asiwaju ninu igbeka oselu akariaye ni orundun ogun. O se ipa pataki si irojinle awon ibasepo akariaye ati igbeka ofin akariaye, be sini iwe re Politics Among Nations, (Oselu Larin awon Orile-ede) to koko je titejade ... | |
Kí ni Iṣẹ-ṣiṣe nípa Kojo Annan? | Kojo Annan ní ìfẹ́ pẹ̀lú ọ̀pọ̀ àwọn ilé iṣẹ́ tuntun ní báyìí, ó sì dá Africa10 sílẹ̀ ní ọdún 2016, ilé iṣẹ́ àwùjọ kan tí ó mójútó ìdàgbàsókè àwọn ọmọ orílẹ̀-èdè Áfíríkà nípasẹ̀ eré ìdárayá àti ẹ̀kọ́ | |
Ṣe àlàyé Margaret Adeoye fún mi. | Margaret Adetutu Adeoye tí wọ́n bí ní ọjọ́ kejìlélógún oṣù kẹrin ọdún 1985 jẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè Britain tó máa ń sáré nínú ìdíje eré-ìdárayá, tó sì máa ń kópa nínú ìdíje onígba mítà.Ó ṣojú ìlú Britain nínú ìdíje igba mítà ní ìlú London, ní ọdún 2012. Ìdíje rẹ̀ tó dára jù fún eré igba mítà wáyé ní ọjọ́ kẹfà oṣụ̀ kẹjọ, ọdú... | |
Kí ni ìtumọ̀ Gay Activists Alliance? | Gay Activists Alliance ( GAA ) ni a da ni Ìlú New York ni Oṣu Kejìlá ọjọ 21, ọdun 1969, o fẹrẹ to oṣu mẹfa lẹhin awọn ìjà igboro Stonewall, nipasẹ awọn ọmọ ẹgbẹ alaigbagbọ ti Gay Liberation Front (GLF). Ni idakeji si Front Liberation, Alliance Activists daduro ati ni pàtàkì ṣe iranṣẹ fun awọn ẹtọ Gay ati Lesbian, sọ ar... | |
Ṣe àlàyé Iṣẹ ṣíṣe káàkiri ayé fún Sammy Adjei. | Adjei jẹ olù múlé akọkọ tí a yán láàyò fún ẹgbẹ́ orílẹ-èdè titi di ọdún 2006, nigbati Richard Kingson di olókìkí. Adjei ni orukọ nínú ẹgbẹ Ghana fún ọdún 2006 African Cup of Nations ni Egypt ati 2006 World Cup ẹgbẹ ni ọjọ kẹtàlá oṣù kàrún ọdún 2006. Adjei ṣe ifarahan kan ni idije naa, gẹgẹbi olùgbéwọlé , nigbati wọn gb... | |
Kí ni Isẹ́ rẹ̀ nípa Ayoka Olufunmilayo Adebambo? | Iṣẹ́ ọ̀jọ̀gbọ́n Ayoka bẹ̀rẹ̀ ní Yunifásítì ìlú Ìbàdàn níbi tí ó ń ti ń fi àwọn iṣẹ́ rẹ̀ kọ̀kan hàn kí ó tó lọ sí Institute of Agricultural Research and Training ní Yunifásítì Ọbáfẹ́mi Awólọ́wọ̀, Ilé-Ifẹ̀. Nígbà tí ó wà ní Ilé-Ifẹ̀, ó kó ọ̀pọ̀lọpọ̀ akitiyan nínú títún àbùdá àwọn elédè ṣe láti mú èrè wá ní títà wọn. Ní ọ... | |
Jọ̀wọ́ sọ nípa Ìgba èwe rẹ̀ ti Iris Apatow. | Apatow ni wọ́n bí ní ọjọ́ Kejìlá oṣù Kẹwàá ọdún 2992, Apatow tí ó jẹ́ ọmọ gbajú-gbajà òṣèré Judd Apatow, tí ìyá rẹ̀ Leslie Mann náà sì jẹ́ òṣèré pẹ̀lú. Ẹ̀gbọ́n rẹ̀ niMaude Apatow. Her father's family is Jewish. Her maternal great-grandmother was of Finnish ancestry. | |
Kí ni Idite nípa Abuja Asopọ? | Fiimu naa ṣe afihan ijakadi fun agbara, owo ati bi nini awọn asopọ ti o ni ipa ni Abuja, Nigeria, ṣe le di ila laarin osi ati ọrọ. Jennifer ati Sophia jẹ abanidije ninu ere yii. Wọn ṣẹlẹ lati jẹ ti idile kanna ati pe wọn ni alaye inu ti iṣẹ apinfunni kọọkan miiran. Sibẹsibẹ, Jennifer jina siwaju ere naa. Nigbagbogbo o ... | |
Jọ̀wọ́ sọ nípa Oju-iwe Kiini ti Atúmọ̀-Èdè (Gẹ̀ẹ́sì-Yorùbá): E. | earl: n; (The man was made as an earl.) irúfé oyè kan ní ilè àwon òyinbó –igbá kerun mógàjí wón fi okùnrin náà se ligbákerin mógaji. | |
Kí ló wà ní Tete aye ati lẹhin nípa Glenn Close? | Glenn Close ni a bi ni Oṣu Kẹta Ọjọ 19, Ọdun 1947, ni Greenwich, Connecticut, si awujọ Elizabeth Mary Hester “Bettine” (née Moore) ati William Taliaferro Close, dokita kan ti o ṣiṣẹ ile-iwosan kan ni Belgian Congo ati ṣiṣẹ bi oniwosan ti ara ẹni si ijọba ijọba Kongo Mobutu Sese Seko . O ni awọn arabinrin meji, Tina ati... | |
Jọ̀wọ́ sọ nípa Irène Joliot-Curie. | Irène Joliot-Curie (12 September 1897 – 17 March 1956) je onimo sayensi ara Fransi, ohun ni omobinrin Marie Skłodowska-Curie ati Pierre Curie ati iyawo Frédéric Joliot-Curie. Lokanna mo oko re, Joliot-Curie gba Ebun Nobel fun Kemistri ni 1935 fun iwari won iranna afowose. Eyi so ebi Curie di ebi to ni awon elebun Nobel... | |
Ṣàlàyé Ìtàn nínú Legit.ng. | Ní oṣù kẹwàá, ọdún 2022, Legit.ng di ilé iṣẹ́ àtẹ́ròyìn jáde àkọ́kọ́ lórí Facebook láti ọwọ́ NewsWhip Ranking. | |
Kí ni (àfikúnàkôkúnìtànká)/ Sufikso nípa Èdè Esperanto? | malsanulo -(mal-san-ul-o) - (láìlágbárabí olókùnrùnaláìleratí kò jámô nkanàìnípáàìlágbára òfin) (èniyàn, çnìkan, olúwarê, alámôrín) | |
Fi Mass action replacing litigation hàn mí nínú Ìrìnkánkán àwọn Ẹ̀tọ́ Aráàlú ọmọ Áfríkà Amẹ́ríkà (1955–1968). | In 1952, the Regional Council of Negro Leadership (RCNL), led by T. R. M. Howard, a black surgeon, entrepreneur, and planter, organized a successful boycott of gas stations in Mississippi that refused to provide restrooms for blacks. Through the RCNL, Howard led campaigns to expose brutality by the Mississippi state hi... | |
Kí ni àwọn ohun pàtàkì nípa Jackie Acevedo? | Jackie Lynn Acevedo Rangel (tí wọ́n bí ní 18 January 1987) jẹ́ agbábọ́ọ̀lù tó wá láti ìlú Mexico, àmọ́ tí wọ́n bí sí ìlú America. Gẹ́gẹ́ bí i agbábọ́ọ̀lù, ipò agbábọ́òlù ata-má-tàsé ló ń gbá. | |
Kí ni ìtumọ̀ Pius Adesanmi? | Pius Adesanmi(Ọjọ́ Kẹtàdínlọ́gbọ́n, Oṣù kejì, ọdun 1972 sí Ọjọ́ Kẹwàá, Oṣù kẹ̀ta, ọdun 2019) jẹ́ ọmọ Orílẹ̀èdè Nàìjíríà tí ó fi ìlú Canada ṣe ibùgbé. Ọ̀jọ̀gbọ́n, òǹkọ̀wé, Onísẹ́ lámèyítọ́ alátinúdá ni, òǹkọ̀wé afẹ̀dáṣẹ̀fẹ̀ àti òǹkọ̀wé sínú ìwé ìròyìn àtìgbàdégbà. Òun ni òǹkọ̀wé ìwé Naija no dey carry last, Àkójọpọ̀ àwọ... | |
Ṣe àlàyé Èdè ìperí wọn fún Amòfin. | Ìyàtọ̀ láàrín Barrister àti Solicitor ni ó jẹyọ nínú ìmọ̀òfin awọn gẹ̀ẹ́sì, tí ó sì jẹ́ wípé púpọ̀ nínú àwọn orílẹ̀-èdè tí Won gba òmìnira kúrò lọ́wọ́ ìmúnisìn àwọn gẹ̀ẹ́sì ni wọ́n ń lo ìlànà òfin gẹ̀èsì, síbẹ̀ wọ́n sọ orúkọ méjèèjì di ọ̀kan. Àwọn orílẹ̀-èdè bíi: New Zealand, Kánádà, India Pakistan, àti US ni wọ́n sọ B... | |
Jọ̀wọ́ sọ nípa Samuel Adeleye Adenle. | Samuel Adeleye Adenle I (1903-1976) jẹ ọba ni ilé Yorùbá . oje Ataoja okandinlogun (Ọba) ti Osogbo ìlú isembaye ti oje olu ìlú ìpínlè Osun. | |
Kí ni Ìsẹ̀mí rẹ̀ nípa Joelle Kayembe? | Ní ọdún 2015, Kayembe ṣiṣẹ́ pẹ̀lú Trace Foundation láti pèsè àwọn ohun-ìkẹ́kọ̀ọ́ fún àwọn ọ̀dọ́mọbìnrin méjì kan. Ní Oṣù kọkànlá Ọdún 2016, ó ṣe ìgbéyàwó ní ìlú Cape Town. | |
Kí ló wà ní Iṣẹ́-ṣíṣe nípa Unlimited L.A? | Láti ọdún 2011, ó ti ṣiṣẹ́ fún ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn òṣèré orin ní dídarí àwọn fídíò orin wọn, pàtàkì Olamide . | |
Sọ fún mi nípa Igbe Ogunso ti Àwọn Ìdíje Òlímpíkì Ìgbà Oru 2004. | The lighting ceremony of the Olympic flame took place on March 25 in Ancient Olympia. For the first time ever, the flame travelled around the world in a relay to former Olympic cities and other large cities, before returning to Greece. | |
Ṣàlàyé ohun tí Agbassa jẹ́. | Agbassa ni oruko okan ninu awon ijoba Urhobo meji to wa ni ijoba ibile Warri South, Delta State Nàìjíríà, ekeji ni Okere-Urhobo. Orukọ 'Agbassa' jẹ ti Ilu Brítánì ti o wa lati orukọ atilẹba rẹ 'AGBARHA', eyiti o tun wa ni lilo. Ọba ti o wa lọwọ ni H.R.M Orhifi Ememoh II. | |
Kí ni Ìlò òróró nípa Òróró? | Óróró lè jẹ́ èyí tí a rí fàyọ láti ara ẹranko, ewébẹ̀ tàbí èyí tí wọ́n fi àwon kẹ́míkà ṣe àgbékalẹ̀ wọn. A lè lo òróró bíi olive oil fún óúnjẹ sísè. A lè lo irúfẹ́ òróró míràn fún àwọn ohun èlò ẹ̀rọ ilé wa bíi ọkọ̀, alùpùpù àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ. A lè lo àwọn òróró bì mineral oil fùn ìtọ́jú àwọn aláàrẹ̀ nílé ìwòsàn, bẹ́ẹ̀... | |
Kí ni Ìpínlẹ̀ Imo? | Ìpínlẹ̀ Imo (Igbo: Ȯra Imo) jẹ́ ìpínlẹ̀ kan ní agbègbè gúúsù-ìlà-oòrùn orílẹ̀ èdè Nàìjíríà, tí ó pín ààlà sí àríwá pẹ̀lú Ìpínlẹ Anambra, Ìpínlẹ̀ Rivers sí ìwọ̀-oòrùn àti gúúsù, àti Ìpínlẹ̀ Abia sí ìlà-oòrùn. Ó mú orukọ rẹ látara odò Imo tí ó ń sàn jákèjádò ààlà ìlà-oòrùn. Olú-ìlú ìpínlẹ̀ náà ni Owerri tí orúkọ ìnagigẹ ... | |
Kí ni Ìgbésí ayé íbẹ́rẹ́ nípa Aret Komlosy? | Ọmọbìnrin alárinrin Patti Boulaye àti Olùdarí eré ìdárayá Stephen Komlosy, Komlosy ni a dàgbà ní Ìlú Gẹ̀ẹ́sì, ṣùgbọ́n gbé ní Nigeria ní ṣókí pẹlú ìyá àgbà rẹ̀. Bí ọmọdé, ó jẹ́ Aṣíwájú Backstroke Junior kan tí Ìlú Gẹ̀ẹ́sì. Ní 1996, lákokò ìsinmi ní Nigeria, Komlosy di olùborí eré-ìje àkọ́kọ́ tí òdómọbìnrin Ẹlẹwà jùlọ ní... | |
Kí ló wà ní Ikole nípa Bakolori Dam? | Ikole idido naa, pẹlu ipele ilẹ, imukuro ati ikole lila run awọn ilẹ oko ti o niyelori ati awọn igi. Àwọn àgbẹ̀ àdúgbò náà di àgbẹ̀ tí kò ní ilẹ̀. Pupọ ko gba ẹsan, tabi ti a fun ni ilẹ asan. Awọn ti o duro ni a fi agbara mu lati gbin awọn irugbin ti a ko mọ gẹgẹbi alikama. Nígbà iṣẹ́ ìkọ́lé, àwọn àgbẹ̀ àdúgbò náà kò n... | |
Jọ̀wọ́ sọ nípa Àmì ẹ̀yẹ ati iyin ti Michael Opeyemi Bamidele. | Ni Oṣu Kẹwa Ọdun 2022, ola orilẹ-ede Naijiria kan ti Alakoso Aṣẹ ti Niger (CON) ni a fun ni nipasẹ Alakoso Muhammadu Buhari . | |
Kí ni Iṣẹ-ṣiṣe nípa Bineta Diop? | Ni ọdun 1981, Diop darapọ mọ International Commission of Jurists, ti se ile ise ajẹfẹtọ eniyan . Ni ọdun 1996,o ṣẹda Femmes Africa Solidarité (FAS)ni ilu Geneva . Diop ṣe alabapin si imuse ipinnu Igbimọ Aabo ti United Nations 1325 ni ọdun 2000. O ṣe alabapin ninu idagbasoke Iwe-aṣẹ Afirika lori Awọn ẹtọ Eniyan ati Awọn... | |
Jọ̀wọ́ sọ nípa Awọn iwe ti a gba ti Margret Rey. | Gbigba Litireso Awọn ọmọde de Grummond ni Hattiesburg, Mississippi, ni diẹ sii ju awọn apoti ọ́ọ̀dúnrún ti awọn iwe Rey ti o wa ni 1973 si 2002. | |
Kí ni Samuel Okwaraji? | Samuel Sochukwuma Okwaraji (19 May 1964 – 12 August 1989) je oni-ise agbaboolu-elese to gba boolu fun Naijiria. O tun je agbejoro lori ofin ibasepo awon orile-ede lati Pontifical Lateran University ilu Romu. O ku nigba to wo lule nitori idina inu okan-aya to ba ni iseju 77k ere boolu ikopa ninu Ife-Eye Agbaye pelu Ango... | |
Sọ fún mi nípa Iṣẹ́ rẹ̀ ti Zainab Gimba. | Lásìkò àpérò ìgbìmọ̀ aṣòfin Commonwealth ìkẹrìnlélọ́gọ́ta (64th CPC) ní ilé ìgbafẹ́ Speke Munyonyo, Kampala ní ọdún 2019, wọ́n yàn Zainab gẹ́gẹ́ bí igbákejì ààrẹ ìgbìmọ̀ aṣòfin àwọn obìnrin Commonwealth ní ilé adúláwọ̀. | |
Ṣe àlàyé Telly Savalas fún mi. | Aristotelis "Telly" Savalas (January 21, 1922 – January 22, 1994) jẹ́ òṣèrékùnrin ti ilẹ̀ Gíríìkì tó tan mọ́ orílè-èdẹ̀ Amẹ́ríkà. Ó gbajúmọ̀ fún orí pípa rẹ̀, àti ohun kíki rẹ̀, bẹ́ẹ̀ sì ni ó gbajúmọ̀ fún ṣíṣẹ́ ẹ̀dá-ìtàn Lt. Theo Kojak nínú fíìmù ajẹmọ́ ìwà-ọ̀daràn tí àkọ́lé rẹ̀ ń jẹ́ Kojak (1973–1978) àti ẹ̀dá-ìtàn Ja... | |
Sọ fún mi nípa Tu ati gbigba ti Oru Lagos kan. | O kọkọ ṣe afihan ni Ọsẹ Nollywood, Paris ni ọjọ 10 Oṣu Karun ọdun 2021 nibiti o ti jẹ ọkan ninu awọn fiimu ẹya 9 ti a yan ni ifowosi si iboju ni ajọdun fiimu agbaye nibiti o ti pin aaye fiimu pipade ni ayẹyẹ fiimu naa. Lẹhin iyẹn, Netflix gba awọn ẹtọ iyasoto si fiimu nibiti o ti ṣe afihan lori pẹpẹ ni ọjọ 29 Oṣu Karun... | |
Sọ fún mi nípa Ìsẹ̀mí rẹ̀ ti Majdouline Idrissi. | Wọ́n bí Idrissi ní ìlú Rabat ní ọdún 1977. Idrissi fẹ́ràn láti máa jíjó ballet, èyí tí ó mú kí ó forúkọsílẹ̀ fún ìkẹ́kọ̀ọ́ nípa ijó ballet náà ní àkókò ìgbà tí ó wà lọ́mọ ọdún mẹ́rin. Nígbà tí ó pé ọmọ ọdún mẹ́rìndínlógún, ó lọ sí ìlú Montreal láti kẹ́kọ̀ọ́ nípa ìṣàkóso òwò. Ó bẹ̀rè sí ní ìfẹ́ sí ṣíṣe eré sinimá lẹ́hìn... | |
Kí ni Christiane Chabi-Kao? | Christiane Chabi-Kao (tí a bí ní 30 Oṣù kẹẹ̀fà, Ọdún 1963) jẹ́ olùdarí eré àti ònkọ̀tàn ọmọ orílẹ̀-èdè Benin. | |
Kí ni Yam pepper soup? | Yam pepper soup jẹ́ oúnjẹ Nàìjíríà tí à ń iṣu puna ṣe. Ó ṣe pàtàkì kí iṣu náà rọ̀. Ọbẹ̀ náà wọ́pọ̀ ni ìhà Gúsù Ìlà-Oòrùn ti Nàìjíríà àti pé díè lára àwọn èròjà ọbẹ̀ yìí ni ehuru, ṣọ̀mbọ̀, oríṣiríṣi ẹran, iyọ̀ àti efinrin. Àwọn èròjà yìí ni ẹ ma fi si nígbà tí iṣu náà bá rọ̀ tí ó sì ti ń di àsáró. | |
Kí ni Marcus Aurelius? | Marcus Aurelius Antoninus Augustus (26 April 121 – 17 March 180) je obaluaye pelu Lucius Verus ni Ile Obaluaye Romu. == Itokasi == | |
Ṣe àlàyé Events fún 4 March. | 1848 - Carlo Alberto di Savoia signs the Statuto Albertino that will later represent the first constitution of the Regno d'Italia | |
Ṣe àlàyé Oju-iwe Keji fún Atúmọ̀-Èdè (Gẹ̀ẹ́sì-Yorùbá): E. | story.) tí ó sàjèjí; tí o yani lénu ó so ìtàn to yani lénu fún wa. Tí ó jẹ́ afikun; àfikun. Wón se àfikùn ìpàdè gbogbo-gbòò. | |
Sọ fún mi nípa Ìtàn-àkọọ́lẹ̀ ti Federal University of Agriculture, Abeokuta. | Ni ọjọ́ kan naa yi ni ìjọba yan ọ̀jọ̀gbọ́n Nurudeen Ọlọrun-Nimbe Adedipẹ gẹ́gẹ́ bi igbákejì aláṣẹ àkọ́kọ́ ti yunifásítì ẹ̀kọ́ ọ̀gbìn Abeokuta. Ọ̀jọ̀gbọ́n Adedipẹ dáwọ́lé iṣẹ́ ni pẹrẹwu lábẹ́ àṣẹ́ ní ọjọ́ kejìdín-lọ́gbọ̀n oṣù kinni ọdún 1988 (28 January 1988). Fún ọ̀pọ̀lọpọ̀ ọdún ni wọ́n ti ṣèsì gba ọjọ́ ti ọ̀jọ̀gbọ́n A... | |
Kí ló yẹ kí n mọ̀ nípa Sola David-Borha? | Olusola Adejoke David-Borha jẹ́ olùdarí àgbà fún ilé ìfowópámọ́ Standard Bank tí ilẹ̀ Áfríkà láti ọdún 2017. Ó jẹ́ olùdarí àgbà fún Stanbic IBTC Holdings títí di oṣù kìíní ọdún 2017. Ò jẹ́ adarí fún ẹgbẹ́ Nigerian Economic Summit Group láti ọdún 2015. Ó darapọ̀ mọ́ àwọn adarí IBTC ní oṣù keje ọdún 1994. Ó jẹ́ ìkan láàr... | |
Kí ni àwọn ohun pàtàkì nípa Àwọn àdúgbò ìlú Iléṣà? | == ILÉSÀ == 1. Àdúgbo: Ìkótì Ìtumò: Ìbí yìí ni àwon omo ogun Ìjèsà gbà lé àwon òtá won ni ìgbà ogun ni èyí, èka ède ló fà á tí ó fi jé Ìkótì. 2. Àdúgbo: Bíládù Ìtumò: Orúko owá ketàlá tó jè ni Ilésà ni Bíládù Arère, ìrántí rè ni won fi so àdúgbò yìí ni orúko rè. Nìgbà tí ò ti dé orí oyè, ó wá gbajúmò débi pé fí àwon èè... | |
Jọ̀wọ́ sọ nípa Ìwé Jóṣúà. | Ìwé Joṣua ni ìwé Bibeli Mimo tó sọ̀rọ̀ nípa Jóṣúà, lẹ́yìn Mósè tó ń jẹ́ adarí àwọn ọmọ Ísírẹ́lì, Jóṣúà ni ó kàn tí ó darí wọn dé ilẹ̀ Kénáánì, tí ń ṣe ilẹ̀ ìlérí Ọlọ́run sí wọn. Jóṣúà, jẹ́ adarí tó ní sùúrù, tó sì jẹ́ akíkanjú ènìyàn. Abbl. == Itokasi == | |
Jọ̀wọ́ sọ nípa Iṣẹ́ olùkọ́ni ti Pete Newell. | Newell padà sí West Coast ní 1954 nígbà tí wọ́n gbà á síṣẹ́ gẹ́gẹ́ bí olùkọ́ni àgbà ní University of California, Berkeley. Newell ṣàṣeyọrí gidigidi ní Cal, tí ó kó àkọsílẹ̀ 119–44 (.730) jọ, tí ó gba àwọn oyè PCC/AAWU mẹrin léraléra láti 1957 sí 1960, tí ó sì darí Golden Bears sí ìfarahàn méjì tẹ̀lé ara wọn nínú eré aṣ... | |
Ṣàlàyé Awọn ọmọ Ọlọfa Ojú-Ìwé 35-36. nínú Ilu Ọyẹ́. | Alaye: Ijalá jẹ apẹrẹ ohun ti o ma nṣẹlẹ nigbamiran nigbati baba kan ba ku, ti o fi awọn ọmọ ati ohun-ini silẹ. Ohun ti i ma ṣẹlẹ nip e olukuluku ninu awọn ọmọ rẹ̀ yio bẹrẹsi dù lati ní ipin ti o tọ́ si on ninu ogun baba wọn, olukuluku ko si jẹ gbà ki nwọn fi ọbẹ ẹhin jẹ on ni iṣu. | |
Ṣàlàyé ohun tí Mario Ervedosa jẹ́. | Mario Ervedosa (ti a bi ni ọjọ kejidinlọgbọn oṣu kaarun ọdun 1998) jẹ oluwe odo orilẹ-ede Angola . O dije ninu idije 50 mita igbaya ọkunrin ninu idije Aquatics World 2017 . == Awọn itọkasi == | |
Ṣe àlàyé Iṣẹ́ fún Somkele Iyamah. | Ó kópa nínú eré 93 Days gẹ́gẹ́ bí dókítà kan tí ó kó àrùn Ẹ̀bólà. Ipa tí ó kó nínú eré yìí ló fà tí ó fi gba àmì ẹ̀yẹ òṣèré to dára jù lọ láti ọ̀dọ̀ ELOY Award. | |
Jọ̀wọ́ sọ nípa ISO 3166-2:CM. | ISO 3166-2:CM ni akoole ninu ISO 3166-2, apa opagun ISO 3166 ti International Organization for Standardization (ISO) tejadesiwe to setumo awon amioro fun oruko awon ipinsabe koko awon orile-ede. == Itokasi == | |
Ṣàlàyé Ìsẹ̀mí rẹ̀ nínú Noufissa Benchehida. | Wọ́n bí Benchehida ní Mòrókò ní ọdún 1975. Ó fẹ́ràn eré sinimá láti ìgbà èwe rẹ̀. Ó kẹ́kọ̀ọ́ ní ilé-ìwé Cours Florent tí ó wà ní ìlú Paris. Benchehida gba oyè-ẹ̀kọ́ nínu ìmọ́ eré-ìtàgé láti ilé-ẹ̀kọ́ gíga Conservatory of Casablanca, bẹ́ẹ̀ ló sì tún lọ sí ilé-ẹ̀kọ́ Ecole supérieure d'hôtellerie et de tourisme à Montpell... |
End of preview. Expand in Data Studio
YAML Metadata Warning:empty or missing yaml metadata in repo card
Check out the documentation for more information.
Yorùbá Academic Wikipedia Q&A Dataset
This dataset contains ~5,000 instruction-style academic question–answer pairs in pure Yorùbá with tone marks, derived from Yorùbá Wikipedia.
Format
Each sample follows:
- instruction: academic question in Yorùbá
- input: empty
- output: academic answer in Yorùbá
Intended Use
- Instruction tuning
- Low-resource language modeling
- Educational assistants
Source
- Yorùbá Wikipedia (cleaned & deduplicated)
- Downloads last month
- 4