Dataset Viewer
Auto-converted to Parquet Duplicate
audio
audioduration (s)
0.06
19.2
speaker_id
stringlengths
5
5
text
stringlengths
9
177
language
stringclasses
1 value
gender
stringclasses
2 values
age_range
stringclasses
3 values
phase
stringclasses
2 values
Q54MY
Kulikuli jẹ́ ìpanu ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tí ó gbajúmọ̀ tí wọ́n ṣe láti inú ilẹ̀.
yoruba
female
18-29
phase 2
WUSNO
Wọ́n kó Samuel Ajayi Crowther lẹ́rú.
yoruba
female
18-29
phase 1
UKMCZ
Ojo wo ni?
yoruba
female
30-over
phase 1
TNPCA
Mo máa wa láti ra ìso náà àti téèpù ìwọ̀n tuntun
yoruba
female
18-29
phase 1
ZHR4X
Mo ṣẹṣẹ gba Snapchat sóri ẹ̀rọ ìbánisọ̀rọ̀ mi.
yoruba
female
18-29
phase 2
Z4PW2
Bẹ́ẹ̀ni, mo rí fakọ́ọ́tì rẹ̀
yoruba
female
18-29
phase 1
L95SJ
ṣe Ade ní olùpilèsè fíìmù yí?
yoruba
female
18-29
phase 1
C36U6
Awon Olóyè naa pinnu lati fi Baba Yemi di oyè Akowe nitori iwa itan-akọọlẹ rẹ.
yoruba
female
6-17
phase 1
Q54MY
O dàbí è pé Ayọ̀ máa ṣe òògùn owó.
yoruba
female
18-29
phase 2
O7XY7
A ti n lo ìlu bàtà láti ayé àtijó ní ilẹ Santeria
yoruba
male
6-17
phase 1
0K8VZ
Ní ilé àwọn ènìyàn lánàá, wọ́n fọ àwọn ìkòkò.
yoruba
female
18-29
phase 1
DAUVB
yinka wo fiimú afíféhán ni ilé iworán naa.
yoruba
female
30-over
phase 1
WWDKX
Àwọn India sọ hindi.
yoruba
male
18-29
phase 1
ELC7E
Òlá ni Oladapo á dárápò mò áwòn ólógùn.
yoruba
male
30-over
phase 2
LCGXO
Wọ́n ó dáríji àwọn ẹlẹ́wọ̀n tó bá hùwà rere wọ́n ó sì tú wọn sílẹ̀
yoruba
male
18-29
phase 1
FPAKJ
Àwọn tọkọtaya máà ń bímọ nínú ìgbéyàwó.
yoruba
female
18-29
phase 1
2JZTK
Ní àtijọ́, omi ewé ni wọ́n fi ń ṣe ọ̀dà
yoruba
female
18-29
phase 1
YT0T2
Ṣé gbogbo fáìlì yẹn ti wà nínú ọ́fìsì mi?
yoruba
male
18-29
phase 2
W8MQ2
àwọn ọlọ́ọ̀pá náà mú ọmọ náà lọ sí ilé àwọn òrukàn
yoruba
female
30-over
phase 2
4NKLY
Ìjọba nípa ọ̀wọ́ àwọn ènìyàn kan ni ètò ìṣèjọba òlígákì.
yoruba
male
30-over
phase 1
IF56O
Ùncle Tayọ̀ tí wà ní ìyàwó láìpẹ̀.
yoruba
female
18-29
phase 2
7OOK5
Á tó ma ṣépè fún gbogbo èèyàn
yoruba
female
30-over
phase 1
UKMCZ
rí dájú pé o tẹlẹ òfin ìsìnkú dada
yoruba
female
30-over
phase 1
8LWEK
Bàbá máa ń pa àlọ́ ni gbogbo alẹ́.
yoruba
female
18-29
phase 1
NM6XG
Isé alágbède ni bàbá mi n ṣe
yoruba
female
18-29
phase 1
HZM4L
Kẹ̀kẹ́ ní àga ìjoko kékeré.
yoruba
female
30-over
phase 2
C6D2E
Dandan ni kí obìnrin ó tọrọ owó oúnjẹ lọ́wọ́ ọkọ rẹ̀.
yoruba
female
18-29
phase 1
72TR9
Ẹka Isakoso ati Iṣiro ti gbalejo awọn apejọ lori awọn ilana inawo
yoruba
male
18-29
phase 1
M1DRD
Máa lọ jẹun ní ilé oúnjẹ Ultima.
yoruba
female
6-17
phase 1
C55LG
Odun díè̩ sé̩yìn, fó̩nrán yàwúù-yàwúù tó ń gbó bí ajá nínú ilé ńlá kan, gbòdekan.
yoruba
female
6-17
phase 1
BHU3N
Awọn ẹdọforo nilo lati wa ni itọju
yoruba
female
30-over
phase 1
M97JE
Diẹ ninu awọn ọmọ-ọwọ ni awọn ọwọ chubby.
yoruba
female
30-over
phase 1
H0LLJ
Ṣé Kọ́lá fẹ́ pa òwe ni?
yoruba
male
18-29
phase 1
CIUZC
Àwọn Olùdásílẹ̀ YouTube ni Jawed Karim,Chad Hurley,àti Steven Chen.
yoruba
female
18-29
phase 1
UU64O
Mo ra musu ní ọjọ́ ìṣẹ́gun.
yoruba
female
18-29
phase 1
MHAQ6
Lẹ́yìn tí ó kanra, Ṣọlá ṣàánú ẹ̀ nígbà tí oòrùn wọ̀, ó sì ṣèlérí láti dára sí i.
yoruba
male
30-over
phase 1
KY5I7
Mo ti bọ ewé mòríngà
yoruba
female
30-over
phase 2
PGFHA
Rárá, wọ́n lè ṣe ọwọ́ ọkọ́ pẹ̀lú irin tàbí igi.
yoruba
male
18-29
phase 1
E9NLH
Láti Ọjọ́ Ẹtì ni mo ti dé
yoruba
female
18-29
phase 1
KSYPO
Bàbá a mi sọ pé ẹni tó bá kàwé ló ń di gómìnà Ìpínlẹ̀, Ààrẹ orílẹ̀èdè, àti gbogbo ibi tí wọ́n ń dì mú ní ẹ̀ka òṣèlú
yoruba
female
18-29
phase 2
HH0CR
Nína èèyàn lé mú ikú lọ́wọ́
yoruba
male
18-29
phase 2
O0RZC
Awọn owo-iworo, bii Bitcoin, ti di olokiki ni ala-ilẹ inawo ti ode oni.
yoruba
female
30-over
phase 1
XHZOC
Trolling pẹlu ṣiṣe awọn asọye akíkanjú lórí ayélujára láti rú esi
yoruba
female
18-29
phase 1
59INZ
Mo wà ní ọdún Ojúde-Ọba lọ́dún tó kọjá
yoruba
male
18-29
phase 2
1ZFDK
Onígbàjámọ̀ yìí fi sùúrù gẹ irun kíkún ọ̀gbẹ́ni yìí.
yoruba
female
18-29
phase 1
HIAR2
Wọn fí inùdí nu ojú ọmọde náà.
yoruba
male
18-29
phase 1
CWMW8
Ṣé o mọ ẹlẹ́rìí náà?
yoruba
male
18-29
phase 1
IJ3BJ
Ètò ọjọ́ orí ṣàgbéga ìwà gidi àti ìbọ̀wọ̀ fún àwùjọ láàárín àwọn akópa
yoruba
male
18-29
phase 1
SRYA7
Adé máa fi ẹja dúdú sì inú ọbẹ̀ náà.
yoruba
female
18-29
phase 2
2GCQP
Ìgbéga kọ̀ọ̀kan wá pẹ̀lú àwọn báàjì ọ̀tọ̀ọ̀tọ̀ nínú ikọ̀ ológun
yoruba
female
18-29
phase 1
3D9SN
Awọn imọ-ẹrọ ti n yọ jade yoo ṣe iyipada awọn ilana ile-ẹjọ, ṣiṣe wọn daradara siwaju sii ni ọjọ iwaju
yoruba
female
30-over
phase 1
HAV7D
Rárá, èmi ni agbẹjọ́rò tí ẹ pè ní àná.
yoruba
male
18-29
phase 1
1KRXX
Gbogbo ènìyàn ṣàjọyọ̀ ní ibi ìsìnkú bàbá arúgbó náà.
yoruba
female
6-17
phase 1
O0GW8
Bẹ́ẹ̀ni, èmi ni mò ń kéwì
yoruba
male
18-29
phase 2
GYV7V
Ọlọ̀pàá ló ní wí pé kí n kúnlẹ̀.
yoruba
female
6-17
phase 1
O8JE2
Ẹ̀mi yòò fẹ̀ lati rá ìbí ìpamọ̀ iwe tuntun ní ọ̀ṣẹ̀ tí n bọ́.
yoruba
female
18-29
phase 1
UU3VS
Okunrin tí o bá yo fìlà rẹ sí òsì túmò sí wípé o tí ní àyà.
yoruba
female
18-29
phase 1
4Y2AK
Nàìjíríà jẹ́ ẹlẹ́ẹ̀kẹrin tí ń pèsè epo rọ̀bì.
yoruba
female
30-over
phase 1
EX7JF
Wọ́n fi àáké gé igi gbígbẹ
yoruba
female
6-17
phase 1
M0FG7
Nọ́mbà ìfowópamósí méèló ni o ní
yoruba
male
18-29
phase 1
TR90J
Sọ fun baba rẹ pe iwọ yoo lọ si ilu Eko!
yoruba
female
18-29
phase 1
6BSDR
Emi yoo tẹsiwaju lati jẹ ẹfọ
yoruba
female
18-29
phase 1
T0W7N
Ṣíṣe ẹ̀tàn àwọn ẹlòmíràn (419) ní í ṣe pẹ̀lú àwọn ètò ẹ̀tàn tàbí ẹ̀tàn.
yoruba
female
30-over
phase 1
II8KP
Iṣẹ́ apọnmi tà ni Bọ́lá ń ṣẹ.
yoruba
female
18-29
phase 2
4BH1U
A ma ra iná to múlẹ̀ sí ọ́fìsì wa.
yoruba
male
18-29
phase 1
OQZKZ
Ewé Ewúró lèyí ìí.
yoruba
female
6-17
phase 1
O0GW8
Lẹ́kkí Port ni ibùdó ọkọ̀ ojú-omi tó jìn jù ní Nàìjíríà
yoruba
male
18-29
phase 2
VAO6L
Igi ni wọ́n fi n se òpó iná láyé àtijó
yoruba
male
18-29
phase 2
5E7GR
Àwọn ìyá a máa mójú tó àwọn ọmọ wọn.
yoruba
male
30-over
phase 1
YT0T2
Gbé òfì náà wá!
yoruba
male
18-29
phase 2
MZLHM
Àdín jẹ́ ọ̀kan lára èròjà tí ó dára jù lọ láti ṣe ìparí
yoruba
male
18-29
phase 2
YT0T2
Gba ìbon náà lọ́wọ́ ẹ̀.
yoruba
male
18-29
phase 2
SRYA7
"Lọ ìgbéyàwó ṣọ́ọ̀ṣì náà!", Ìyá rẹ̀ pariwo
yoruba
female
18-29
phase 2
4Z52Q
Ó jẹ́ obìnrin oní ọkàn tútù
yoruba
male
18-29
phase 1
6KW8G
Sé obìnrin náà yíì o jí owó mi
yoruba
female
6-17
phase 1
O4L4N
Àwọn ọkùnrin nìkan ni wọ́n ti jẹ́ ààrẹ ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.
yoruba
female
18-29
phase 1
KQWBJ
Ó ma ra ago olówó ńlá fún mi.
yoruba
female
18-29
phase 1
2NA7U
Ọ̀gá ilé-ìwé sọ pé, àwọn kan jí kòǹpútà láti inú ìyàrá kòǹpútà lọ́sẹ̀ tó kọjá
yoruba
male
18-29
phase 1
FWJFI
Igi ni a máa ń fi ń lu ẹ̀wà ní ayé àtijọ́, kí ó tó di wí pé ẹ̀rọ dé
yoruba
male
30-over
phase 1
Q097Z
Bẹẹni, ó wá sí ibi ìdáná
yoruba
male
30-over
phase 1
1WS51
Òògùn àìsàn ibà ni Adémidé lò ní alé àná
yoruba
female
30-over
phase 1
W8MQ2
Wọn yóò kó Ìbọn àwọn ológun lọ fún àwọn ọlọ́ọ̀pá ní ọ̀la
yoruba
female
30-over
phase 2
FAGZG
Paṣipaarọ owo-owo ti jẹ ọna pipe gbogbogbo fun igbega olu lati ibẹrẹ rẹ
yoruba
female
18-29
phase 1
AADVW
Bàbá yóò pàlọ́ fún wa ní alẹ́.
yoruba
male
30-over
phase 1
MI27N
Wọ́n máa tó wá fún wa ààbọ̀ ibi tí wọ́n bá iṣẹ́ ilé náà dé.
yoruba
female
18-29
phase 1
8C1U5
Pàn frying yoo jẹ ki sise ni igbadun diẹ sii
yoruba
male
30-over
phase 1
LVIAE
Àbúrò ìyá mi ló fi aṣọ náà ranse sí mi láti Texas.
yoruba
female
30-over
phase 1
FQ192
Gbọ́ ìtàn tí mò ń sọ!
yoruba
male
6-17
phase 1
SESAF
Awọn alufaa yóò lọ fun ayẹyẹ kan ni ọsẹ ti n bọ.
yoruba
female
18-29
phase 1
HNSNF
Àwọn ọmọdé máa kópa nínú eré ìdíje eré sísá.
yoruba
female
18-29
phase 2
U7LKC
Bàbá Kọ́lá ra ilé iṣẹ́ ìròyìn.
yoruba
male
18-29
phase 1
FZIVE
Ilé aláró dà?
yoruba
female
18-29
phase 1
ELC7E
Ijètá ni Bayo di lèftènánti abi?
yoruba
male
30-over
phase 2
I8Y7I
ilé alájà méjì nílò owó púpọ̀ láti kọ́ ọ.
yoruba
female
30-over
phase 2
4YIRH
Olú bá pẹ́dà ọ̀kadà Adé jẹ́.
yoruba
male
18-29
phase 1
HZM4L
Bẹ́ẹ̀ ni, ó gbé báágì ìyá rẹ̀.
yoruba
female
30-over
phase 2
N5YJT
Wọ́n lo Igi ọsan láti gbọ́ oríṣìí àìsàn láyé àtijọ́ kí òògun òyìnbó tó dé.
yoruba
female
18-29
phase 1
HN1Q2
Bólú gbàgbé kọ́mú rẹ̀ sílé
yoruba
male
18-29
phase 1
BF2DL
Erythromycin jẹ́ àpẹrẹ oògùn tí ń fọ ẹ̀jẹ̀ mọ
yoruba
male
18-29
phase 1
K0D61
Aní ìpanu ní ọ́fìsì wa ní ìgbà kan sẹ́yìn.
yoruba
female
18-29
phase 1
End of preview. Expand in Data Studio
README.md exists but content is empty.
Downloads last month
34