Dataset Viewer
Auto-converted to Parquet Duplicate
audio
audioduration (s)
0.06
19.6
speaker_id
stringlengths
5
5
text
stringlengths
7
194
language
stringclasses
1 value
gender
stringclasses
2 values
age_range
stringclasses
3 values
phase
stringclasses
2 values
II8KP
Ni akọkọ na, aini igbẹkẹle wa laarin wa.
yoruba
female
18-29
phase 2
RDCXQ
Tolú nlo ògùn ní ìlòkulò
yoruba
female
18-29
phase 1
3LLA0
1. Se àgbò fún mi.
yoruba
male
18-29
phase 1
AIMX8
Gbé ọbẹ̀ náà sì inú fíríjí tí ó bá ti dé
yoruba
female
30-over
phase 1
8NTXE
Wọn má máa tá èso ní gbogbo ibi ni ọjọ́ iwájú.
yoruba
male
6-17
phase 1
FYP5E
Tobiloba béèrè bóyá òun lè fi àtẹ̀jíṣẹ́ ránṣẹ́ sí i lórí Whatsapp
yoruba
male
18-29
phase 1
GDGSD
ẹgbẹ àwọn àgbẹ̀ ní ìdibọ wọn sì fí ọgbẹni bábájídé jé alága tuntun
yoruba
female
18-29
phase 1
EAGBK
A4 pepà ni wọ́n ń sábà máa ń lò nílé iṣẹ́ atẹ̀wẹ́tà
yoruba
female
18-29
phase 1
IMMVO
Àwọn ọmọ woama ń ṣeré nínú ọgbà
yoruba
male
18-29
phase 1
3O6YU
Áwòn ólógùn tó lò si Kaduna á pádà lòlá
yoruba
male
18-29
phase 1
LA0Y9
Àwọn olùkọ́ máà ní ìpàdé.
yoruba
female
18-29
phase 2
ECGRM
Wọ́n bí mi sínú ẹ̀sìn Ìsìláàmù ni, inú mi sì máa ń dùn pé Mùsùlùmí ni mí
yoruba
female
18-29
phase 1
OZCG2
Lo ra àwon ìpèsè oúnje
yoruba
female
30-over
phase 2
43FB0
ṣe iwọ yóò mu eko ?
yoruba
female
30-over
phase 2
NKGIM
Àṣàkẹ́ yóò kiri Máńgò lọ ní ọwọ́ ìrọ̀lẹ́
yoruba
female
6-17
phase 1
2BSPI
Mojísọ́lá fẹ́ gbin ẹ̀gẹ́ sí oko rè.
yoruba
male
18-29
phase 1
349RS
Irin wúlò fún ìgbékalẹ̀ tí ó dúró dáadáa.
yoruba
male
30-over
phase 1
4XT0F
ìjọba ológun lo tọ́ sí àwọn orílẹ̀ èdè kan.
yoruba
female
18-29
phase 2
MZLHM
Ìdílé pẹ́là gbà yìí fún idán pípa ni ìgbàkan
yoruba
male
18-29
phase 2
HH0CR
Ìyá à mí fẹ́ràn àgbàdo sísè
yoruba
male
18-29
phase 2
LCGXO
Ṣé àwọn ni ẹlẹ́wọ̀n?
yoruba
male
18-29
phase 1
TF61S
Ṣé wà á bá mi ra àtíkè bọ̀ nílé ìtajà tó ń lọ?
yoruba
male
30-over
phase 1
Y9M2Q
Agbèéfín-okọ̀ náà tú èéfín sínú afẹ́fẹ́.
yoruba
female
18-29
phase 1
II8KP
Bísí jí gègé ìkọ̀wé mi
yoruba
female
18-29
phase 2
LTZQW
Mo sọ pé kí ẹ mú mí lọ ọ̀dọ olorì!
yoruba
male
30-over
phase 1
HPTGN
Ẹ kú oriire ni a ki ẹni tó bímọ
yoruba
female
18-29
phase 2
DMXGW
irú eso wo ni a tun le fi se jam
yoruba
female
6-17
phase 1
MOLZM
Talo ṣe eèwò?
yoruba
female
30-over
phase 1
AA6NB
Bẹ́ẹ̀ni, àwọn oníṣègùn máa de oyún náà
yoruba
female
30-over
phase 1
V77RP
Ilé oúnjẹ ìgbàlódé KFC bẹ̀rẹ̀ ni orílẹ̀ èdè Nàìjíríà ni ọdún ẹ́sàn-án-lé-lẹ́gbàá
yoruba
female
18-29
phase 1
LA0Y9
Agbójúlógún fi ara rẹ̀ fóṣì ta
yoruba
female
18-29
phase 2
OZCG2
Ma pa lábàlábà yen !
yoruba
female
30-over
phase 2
CCO6H
Àbúrò mi ọkùnrin tí gbogbo abọ sínú ilé ìdáná lẹyìn tó jẹun tán.
yoruba
male
18-29
phase 1
ZHR4X
Èmi ni asojú kíláásì mi fún kíláásì mi.
yoruba
female
18-29
phase 2
FB2CO
Private recruit náà ń ṣiṣẹ́ kárakára.
yoruba
male
18-29
phase 1
Q6KV2
Nígbà wo ni ó kọ́ ọkọ̀ wíwà.?
yoruba
female
30-over
phase 2
BVQGV
Àlàó ti dá aṣọ tó rà lọ́dún tó kọjá padà.
yoruba
male
30-over
phase 1
XMP7G
Aremu dára nínú àwọ̀
yoruba
male
18-29
phase 1
II8KP
Ọ̀gá yìí ó bá wà ra àwọn piini-ofiíísì síí
yoruba
female
18-29
phase 2
59INZ
Rárá, kì í ṣèké
yoruba
male
18-29
phase 2
G3QJO
Njẹ àwọn akẹ́kọ̀ọ́ kò wa ní àna?
yoruba
male
6-17
phase 1
BN1ZC
Ẹ̀sìtẹ́ṣọ́nù ti bàjẹ́.
yoruba
female
18-29
phase 2
72G2C
Ìṣe oníròyìn ni ṣade ń ṣe
yoruba
male
30-over
phase 1
2WJTR
Àwọn olóyè ni akẹ́kọ̀ọ́ tí wọ́n fún ní ojúṣe pàtàkì láti pa ilé ìwé mọ́
yoruba
female
18-29
phase 2
4RO3C
Kọ́lá máa ra abọ kúlíkúlí kan wá ilé lọ́sẹ̀ tó ń bọ̀
yoruba
female
18-29
phase 1
9HK10
Ẹ̀ẹ́dẹ́gbẹ̀ta náírà ni mo wọ mọ́tò Yaba sí Osodi
yoruba
female
18-29
phase 1
M0FG7
Ọdún mélòó ni a fi máa fi ilẹ̀ yìí sílè kí a tó padà gbin ǹkan síbẹ̀?
yoruba
male
18-29
phase 1
O0GW8
Tọ́lá sọ kámẹ́rà rẹ̀ nù lọ́sẹ̀ tó kọjá
yoruba
male
18-29
phase 2
8SU86
Ṣé ó nu tábìlì ?
yoruba
male
18-29
phase 1
CTYSP
Awọn tabili ọfiisi le rọpo nipasẹ awọn ibi iṣẹ oni-nọmba ni ọjọ iwaju
yoruba
female
6-17
phase 1
47S2P
Ọkọ ni olórí ilé.
yoruba
female
30-over
phase 1
K4GZK
Ta ni I fe arabinrin rẹ?
yoruba
male
18-29
phase 1
VJ3PT
Ojo yóò fẹ́ràn láti fún omi tangerine náà jáde
yoruba
female
30-over
phase 1
QWZAL
Mo lọ sí oko láti ká àgbàdo
yoruba
male
30-over
phase 1
80ZPE
Ọlá ni a máa pín àwọn ọtí agbára náà fún wọn.
yoruba
female
18-29
phase 1
KY5I7
Tolú ṣubú lulẹ̀ ni ilé ìwẹ̀,o fi órí gbá sinkii.
yoruba
female
30-over
phase 2
W8MQ2
Ẹran tí o rà lánàá kì í ṣe ẹran ẹlẹ́dẹ̀ ṣùgbọ́n ẹran màlúù.
yoruba
female
30-over
phase 2
9CYPC
Ìyá rẹ̀ ń ṣe iṣẹ́ ní ilé ìwòsàn
yoruba
male
18-29
phase 1
W8MQ2
ona èrè ọkọ òfurufú tí ṣetan fún ọkọ òfurufú tí nwọle.
yoruba
female
30-over
phase 2
7R76Z
Bẹẹni, mo mọ awakọ̀ náà
yoruba
female
30-over
phase 1
Q6KV2
Ǹjẹ́ ọkọ̀ ojú omi ni àwọn apẹja lò lánàá?
yoruba
female
30-over
phase 2
64E8A
Àwọn father ni ó sábà máa ń jẹ́ olórí ẹbí.
yoruba
male
18-29
phase 1
CSMDP
Kò mọ̀ pé ẹ̀sìn òkèèrè lòdì sí sísọ̀rọ̀ òdì sí Ọlọ́run.
yoruba
female
18-29
phase 2
NSVL6
È̩gbó̩n Kó̩lá kó̩ o̩ bí yóò s̩e lo èmú kékeré s̩ùgbó̩n ó ti gbàgbé
yoruba
female
6-17
phase 1
FJ41K
Obìnrin náà gbé ọmọ náà sí orí àga
yoruba
female
18-29
phase 1
4M7P2
Ní ayé àtijọ́, alárinà ló máa ń ṣojú ọkùnrin láti bá obìnrin sọ̀rọ̀.
yoruba
male
30-over
phase 1
DL8T9
Àwọn míràn fẹ́ràn kí ọmọ kún ilé.
yoruba
male
30-over
phase 1
92GPR
Bẹ́ẹ̀ni, mo máa kọ orin ìbílẹ̀.
yoruba
female
18-29
phase 1
PMI6A
Bẹ́ẹ̀ni ó wà níbí
yoruba
male
30-over
phase 1
2SCF8
Èmi àti àwọn ọ̀rẹ́ mi gbá bọ́ọ̀lù lọ́wọ́.
yoruba
female
18-29
phase 2
K464B
Ìṣe onidírì ni ìyá túnjí ń ṣe.
yoruba
male
18-29
phase 1
XTEFB
Ni oṣu to kọja, a rọpo fáànù aja fun ṣiṣe to dara julọ.
yoruba
female
18-29
phase 1
W8MQ2
Àwọn olùkọ́ ní ìpàdé nínú ìyàrá àwọn olùkọ́ ní ago méjì ọ̀sán lánàá.
yoruba
female
30-over
phase 2
VH0LI
Ṣé gbogbo àwọn aláfẹ́ ló ń mu ọtí líle?
yoruba
female
30-over
phase 1
TB888
Emi yoo nifẹ lati kọ bi a ṣe le hun aso
yoruba
female
18-29
phase 1
II8KP
Ọ̀làjú yóò jẹ́ kí àwọn ènìyàn fojú di èwọ̀ ní àwùjọ Yorùbá.
yoruba
female
18-29
phase 2
QBWT6
Awọn ẹya aabo ti o ni ilọsiwaju yoo ṣepọ si awọn ọja ọmọ iwaju
yoruba
male
18-29
phase 1
TUJLE
Rárá, mi ò rí máníjà ẹ̀ka nígbà tí mo lọ ṣe ìfisùn náà lánàá.
yoruba
female
18-29
phase 1
MGWAM
Ó yẹ kí o ti gba ògùn yẹn nílé ìtajà ògùn!
yoruba
female
18-29
phase 2
XPYBH
Ṣé o ń rán aṣọ àńkò iṣẹ nọ́ọ̀sì?
yoruba
female
18-29
phase 1
M1KTP
Àwọn oloyun o gbọdọ lò òògùn ibà.
yoruba
male
30-over
phase 1
OTIMD
Awọn dòkítà ọ̀unjẹ ṣẹ̀ iranlọ́wọ̀ fún ènìyàn lati jẹ̀ún dára jùlọ̀ fún ìlẹ̀rà wọn àti awọn iwúlọ́ ìṣòogùn kàn pátò.
yoruba
male
30-over
phase 1
YYE5W
Adé ń tọ́jú àwọn aláìsàn lọ́wọ́
yoruba
female
18-29
phase 1
KSYPO
Olùgbaniwọlé Fáṣitì Èkó fún ọdún 2017 ni arábìnrin Ipaye
yoruba
female
18-29
phase 2
IF56O
Orí Fáànù onídùúró máa ń yí láti ẹ̀gbẹ́ kan sí ẹ̀gbẹ́ kejì.
yoruba
female
18-29
phase 2
4XT0F
Yin ìbọn náà!, corporal kigbe.
yoruba
female
18-29
phase 2
OVFI5
Ó kọ́ ilé ilẹ̀.
yoruba
female
18-29
phase 2
SH405
Bẹ́ẹ̀ni, mo ní ọ̀pọ̀lọpọ̀ ọ̀rẹ́.
yoruba
female
30-over
phase 1
DYBU5
Ṣe Ìtọ́jú ojú ẹ.
yoruba
female
30-over
phase 1
N9GRE
ketchup yẹn dà
yoruba
female
18-29
phase 1
1ZFDK
Láàbù Bàọ́lọ́jì náà yóò gbàlejò àwọn akẹ́kọ̀ọ́ tuntun
yoruba
female
18-29
phase 1
KY5I7
Tani akẹ́kọ̀ọ́ nọ́ọ̀sì tí ó wá sí ibùgbé rẹ lánàá?
yoruba
female
30-over
phase 2
JO8XJ
Ní oṣù tó ń bọ̀, àwọn ọmọ ilé ìwé yóò kópa nínú ìdíje eré ìdárayá
yoruba
female
30-over
phase 1
V9N11
A máa lo balùwẹ́ lónìí
yoruba
female
30-over
phase 1
6P5HO
Àwọn onímọ̀-èrọ jẹ́ òṣìṣẹ́ tí ó tó láti tún Ẹ̀rọ amúlẹ̀tutù ṣe
yoruba
female
6-17
phase 1
YT0T2
Gbogbo àwọn ohun èlò ìṣeré ilé-ìwé àwọn Bísí ni ó ti fẹ́ẹ̀ bàjẹ́ tán
yoruba
male
18-29
phase 2
M4J0U
Ìkòkò ìdín-nǹkan ṣe pàtàkì fún dídín ẹran.
yoruba
female
30-over
phase 1
426GC
Èmi ni mo mú aṣo ìbora na.
yoruba
female
18-29
phase 1
O0GW8
Ilé-ìwé fún awọn ọmọdé afọ́jù mú awọn ọmọ wọn láti kọ́pa nínu idíjè orin ní ànà
yoruba
male
18-29
phase 2
3QGJH
Fọlá, wà á lọ sí ilé àwọn ọmọ aláìníìyá náà.
yoruba
female
18-29
phase 1
End of preview. Expand in Data Studio
README.md exists but content is empty.
Downloads last month
12