Dataset Viewer
Auto-converted to Parquet Duplicate
audio
audioduration (s)
0.06
34
speaker_id
stringlengths
5
5
text
stringlengths
7
191
language
stringclasses
1 value
gender
stringclasses
2 values
age_range
stringclasses
3 values
phase
stringclasses
2 values
CCDO7
Ṣé o lè gbàgbé pé ẹ̀wọ̀n ni Jídé ti ń bọ̀?
yoruba
female
18-29
phase 1
VA7RM
Àwọn ilé-oúnjẹ yóò kún fún àwọn oníbàárà tó ń gbádùn oúnjẹ aládùn wọn.
yoruba
male
18-29
phase 1
SMXL6
Mo ń ṣe àyèwò re pẹ̀lú tẹsitósíkóòpù
yoruba
male
30-over
phase 1
HZAHG
Titi sé èwà lànã
yoruba
female
18-29
phase 1
MZLHM
Olú máa fọ ẹnu rẹ̀ nínú síńkì lójoojúmọ́.
yoruba
male
18-29
phase 2
W8MQ2
Àwọn ọmọ ilé-ìwé máa ń ṣiṣẹ́ lórí oko ilé-ìwé ní gbogbo ọjọ́ ẹtì.
yoruba
female
30-over
phase 2
O0RZC
Èpè jẹ́ ìwà búburú
yoruba
female
30-over
phase 1
2OXGE
Ọ̀pọ̀lọpọ̀ ìgbésẹ̀ lówà sí ìgbéyàwó.
yoruba
female
18-29
phase 1
FAGZG
Iwọn teepu ṣe iwọn gigun ni deede
yoruba
female
18-29
phase 1
2SCF8
Ọ̀gbẹ́ni Kọ́lá, gbé àpò yẹn fún mi.
yoruba
female
18-29
phase 2
FLC1Y
Emi yoo fẹ lati ri amọkoko
yoruba
female
6-17
phase 1
ZACTG
Ṣé alágbàsè náà máa lo ọlọ tàbí ẹ̀rọ fún ata náà?
yoruba
male
18-29
phase 1
Q54MY
Mo máa dá imú mi lu.
yoruba
female
18-29
phase 2
ELC7E
àwọn òbí ré rà insuranci fún ilé wón ní ọdún mẹwàá sẹyìn
yoruba
male
30-over
phase 2
LRMKP
A máa ṣe orò ìdílé fún ọmọ tí a bá ṣẹ̀ṣẹ̀ bí.
yoruba
male
30-over
phase 1
HNSNF
Ábèbè náà wà lórí tábìlì
yoruba
female
18-29
phase 2
ID6DU
Mọ́ lọ sí Dunamis ni Lugbe lọ́sẹ̀ tó kọja, ó tóbi púpọ̀.
yoruba
male
30-over
phase 1
Z2Q9X
Sọlá máa tún àwọn ihò iná ara ilé wa wò
yoruba
female
30-over
phase 1
CSMDP
Ata wà ní oríṣiríṣi ní ìwọ̀n
yoruba
female
18-29
phase 2
WN9Q2
Bàtà gogoro máà ń jẹ́ kí esè ro Tayo.
yoruba
female
18-29
phase 1
HW4A1
Bí ojú ọjọ́ ṣe rí máa ń ní ipa lórí àkókò tó ọkọ̀ ojú omi máa rìn
yoruba
female
30-over
phase 1
LA0Y9
Ẹlẹ́rìí náà bẹ̀rẹ̀ sí í ṣe ìjẹ́rìí lọ́nà tí kò yẹ
yoruba
female
18-29
phase 2
HZM4L
Bẹ́ẹ̀ni, bàbá mi rí mi ní gbọ̀ngàn àpéjọ náà
yoruba
female
30-over
phase 2
SE6G6
Ṣe iwọ yoo ṣe akpụ̀ àti ègúṣí fún mi nigbamíí ti mo ṣabẹwo?
yoruba
female
30-over
phase 1
UN6VG
Wò ó bí ojú ọjọ́ yìí ṣe sáré yípadà lójijì
yoruba
female
30-over
phase 1
UVP6G
Ìyá yẹn ń fi ìfẹ́ hàn sí ọmọ kan ju ìkejì lọ
yoruba
male
18-29
phase 1
39965
Ìyá mi fún mi ni okòólégbèfà-o-lé-mérin náírà nígbà tí wón jáde
yoruba
male
30-over
phase 1
91XMT
Mo fẹ́ bá Ẹ̀gbọ́n mi de ìdí fún ọmọ wọn.
yoruba
male
30-over
phase 1
7TZW9
Ó ṣòro láti mọ àwọn tó ń ṣiṣẹ́ egboògi olóró.
yoruba
male
18-29
phase 2
TVXJ7
Wọn máa kọ́ yàrá ìkàwé ńlá fún ẹ̀ka wá ní oṣù tó ń bọ̀.
yoruba
female
18-29
phase 1
BXQ9S
Kárọ́ọ̀tì ni wón sọ wípé ó dára fún ojú.
yoruba
female
18-29
phase 1
O0GW8
Èèwọ̀ ni kí Ọba wo inú adé orí rẹ̀ ní ilẹ̀ Yorùbá
yoruba
male
18-29
phase 2
YOQQG
Muyiwa ni sikolaṣipu lati kawe ni Ilu Lọndọnu
yoruba
female
18-29
phase 1
HNSNF
Ọmọ náà ni áwọ̀ pupa.
yoruba
female
18-29
phase 2
KJQOP
Yàrá ìkàwé ni a wà ní àná ti olórí ilé ẹ̀kọ́ wà ní àná
yoruba
male
18-29
phase 1
5OVY6
Jẹ ki a lọ si ayẹyẹ Oke Ibadan.
yoruba
male
18-29
phase 1
1ZFDK
Àwọn bátìrì náà yóò di aláìlera ní ọ̀sẹ̀ tó ń bọ̀.
yoruba
female
18-29
phase 1
Y7IV4
Ẹgbẹ́ òkùnkùn ní oríṣiríṣi àwùjọ.
yoruba
female
18-29
phase 1
GYV7V
Àwọn tí ó ń wa ọ́kadà náà ní gáréjì
yoruba
female
6-17
phase 1
E2TI4
Ọ̀gẹ̀dẹ̀ tí mo kó sínú àpò tí tán.
yoruba
female
18-29
phase 1
ZLOOP
Ǹjẹ́ o ní òbí?
yoruba
male
18-29
phase 2
KUK6R
Apọ̀jù Ẹmu mímu máa ń pani
yoruba
female
18-29
phase 1
0EA9E
L'ọ́dún díẹ̀ sẹ́yìn, isaka àti ikoro ni wọ́n lù nígbà àwọn ayẹyẹ ìbílẹ̀
yoruba
female
18-29
phase 1
QI89N
béèni má lọ ọjà èso tí kano lọsẹ tí n bọ
yoruba
male
18-29
phase 1
E69XO
Báwo ni àwọn ènìyàn ṣe ṣe nígbà tí wọ́n mú wọn tí wọ́n parọ́ nípa ìwà wọn?
yoruba
male
18-29
phase 1
U09PH
Bẹ́ẹ̀ ni, a o di ọmọ orogún
yoruba
female
18-29
phase 1
QG4N9
Mo máa ń ya irun mi pẹ̀lú òòyà dúdú ńlá.
yoruba
female
18-29
phase 1
HH0CR
Awogbaààrùn ni oògùn parasítámọ̀ jẹ́
yoruba
male
18-29
phase 2
CSMDP
Ìṣèjọba ìjẹgàba máa ń parẹ́ tí a bá ń lo ìṣèjọba àpapọ.
yoruba
female
18-29
phase 2
WH65Z
Yàrá adarí ilé ẹ̀kọ́ wà tóbi púpọ̀
yoruba
female
18-29
phase 1
BCVY1
Má Ję olóòtọ́!
yoruba
male
30-over
phase 1
3ZHTH
Àga isẹ ni ibiti olùkankan tí máa ń ṣe ọ̀pọ̀lọpọ̀ isẹ rẹ
yoruba
female
18-29
phase 1
F7KH2
Kété tí mo dìbò tán ni mo gba ilé lọ.
yoruba
male
18-29
phase 1
DBM3L
Ṣé Bàbá rẹ̀ ń sún nì?
yoruba
female
18-29
phase 1
DHGUM
Mà á ra panadol.
yoruba
female
30-over
phase 1
EYUO7
Ile ile oloke meji to dara wa lẹba opopona naa
yoruba
female
30-over
phase 1
45M93
Mò gbèrò láti lo ọkọ ojú irin lọ sí Abẹ́òkúta ní ọjọ́ ìṣègun
yoruba
male
6-17
phase 1
W8MQ2
Gíláàsì ìdáàbòbọ̀ ọkọ̀ náà fọ́ nígbà tí ijamba kékeré kan ṣẹlẹ̀.
yoruba
female
30-over
phase 2
L15H4
Àyẹ̀wò ṣe pàtàkì nínú ètò ìtọ́jú.
yoruba
male
30-over
phase 1
NDET0
Mùsùlùmí le fẹ́ ìyàwó mẹ́rin.
yoruba
female
6-17
phase 1
MF6K9
Ebi pẹlu aya kan ati ọkọ kọn rọrùn.
yoruba
female
30-over
phase 1
OZCG2
Ẹ̀ka ti iṣẹ́-ọ̀nà máa ń wà fún àwọn tí ó ń ka èdè.
yoruba
female
30-over
phase 2
QZ3W6
Gbé lọ sí ọgbà ẹ̀wọ̀n Agodi ní ọ̀la!
yoruba
male
18-29
phase 1
KSYPO
Pùròjẹ́tọ̀ ni olùkọ́ fi kọ́ wa ní ìṣirò
yoruba
female
18-29
phase 2
PYFIU
Rárá, WhatsApp nìkan ni mo ní.
yoruba
female
18-29
phase 1
VFKYO
Awọn alúfaa mètá ló wá ṣé adúrá nibi isinkú baba Johnson ni ijètá
yoruba
female
30-over
phase 1
EAE95
Ìbẹ̀rẹ̀ Tayo sínú iṣẹ́ ìṣègùn jẹ́ ìṣẹ̀lẹ̀ pàtàkì.
yoruba
male
18-29
phase 1
UVEJ2
Òlògbò mi fi ẹ̀kaná rẹ yà àsọ ìrọrì mì
yoruba
female
30-over
phase 1
4FR3A
Ó ìbùkún fún ọmọkùnrin tó fún ní 5-alive.
yoruba
female
30-over
phase 1
O4L4N
Ẹgbẹ̀rún ó lẹ́ àádọ́ta-lé-lẹ́gbẹ̀rún ó ń bọ̀ ṣáájú ẹgbẹ̀rún kan ó lẹ́ ẹ̀ẹ́dẹ́gbẹ̀ta.
yoruba
female
18-29
phase 1
HPTGN
Olu ṣe ipò òjìléní-ẹ̀ẹ́dẹ́gbẹ̀ta nínú ẹgbẹ̀rún kan
yoruba
female
18-29
phase 2
O0GW8
Dókítà ojú fún Bimpé lóògùn ojú fún ojú rẹ̀
yoruba
male
18-29
phase 2
IBBF1
Sé ìdánilékòó niípa oyún le mú àdínkù bá ...
yoruba
male
18-29
phase 1
TGB73
Táwà ma to ṣe oúnjẹ tán
yoruba
female
6-17
phase 1
W8MQ2
Arábìnrin náà yóò ṣe ẹ̀wà ní ọjọ ẹtì
yoruba
female
30-over
phase 2
GFQXI
Bí ẹ̀fọn bá jẹ́ èèyàn jù ó lè fa ibà
yoruba
female
18-29
phase 1
WX54M
Àbúrò mi ọkùnrin ma bẹrẹ ilé-ìwé ni ìparí ọsẹ ti o mbọ.
yoruba
male
30-over
phase 1
EX2CK
E̩ran ìgbín jé̩ èyí tí kò ní òrá tí ó sì ní omi
yoruba
female
18-29
phase 1
43FB0
Ta ni yóò jẹ ẹyin dídín?
yoruba
female
30-over
phase 2
YT0T2
Ṣé o n jókòó sí abẹ igi?
yoruba
male
18-29
phase 2
XLLMX
Ogún náírà ló wà lọ́wọ́ mi.
yoruba
male
6-17
phase 1
A64XD
ràrá Tóbi kò sì ní oko.
yoruba
male
6-17
phase 1
YT0T2
Itọ ṣuga ati ẹ̀jẹ̀ ríru lo maa pa alaigbon
yoruba
male
18-29
phase 2
RIA0Z
Ni ìparí ọdun yi, a yóò fẹ láti ni ìjábò ti ilé ìtójú
yoruba
female
18-29
phase 1
VUV3K
Mo ní kí o pọn ìkòkò náà.
yoruba
male
18-29
phase 1
FB1SM
Ọ̀nà ìdáná tí ó wọ́pọ̀ ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà ní bíbọ oúnjẹ
yoruba
male
30-over
phase 1
W8MQ2
Ẹ̀rọ ìfọṣọ yìí ń lo iná.
yoruba
female
30-over
phase 2
BN1ZC
Sọ fún mi nípa ìrírí rẹ ní Liverpool
yoruba
female
18-29
phase 2
L88Q7
Orùkà jẹ́ ọ̀kan lára àmì láti fi ìfẹ́ hàn láàárín lọ́kọ-láya.
yoruba
female
30-over
phase 1
DWXC9
Oba ko feran eran didin
yoruba
female
18-29
phase 1
IF56O
eyan gbọdọ kì àná rè Dàda
yoruba
female
18-29
phase 2
P73VN
Wọ́n má ń rí apẹ̀rẹ̀ lára igi ọ̀pẹ
yoruba
female
30-over
phase 1
1SX0Y
Kí Wálé fi ìsebẹ̀ díẹ̀ sínú oúnjẹ yẹn tí ń bá jáde
yoruba
male
18-29
phase 1
YTOJK
Káfíǹtà ṣe àṣìṣe nígbà tí ó ń gé pákó.
yoruba
female
18-29
phase 1
VBGAM
Ilé, ò̩nà, afárá, ilé ìfowópamó̩ pò̩ ní agbègbè ìlú
yoruba
female
6-17
phase 1
Z2EVY
Béèni, mọ tí gbà àpò mí lówó arábìnrin mí.
yoruba
female
18-29
phase 1
QID8H
A kì í pé olótùú rédíò nígbà kan.
yoruba
male
6-17
phase 1
O8JE2
Ẹ̀mí yóò gé ìrùn mí ni ọ̀lá.
yoruba
female
18-29
phase 1
FEEK8
Ta ló máa gba àwọn òdòdó yẹn fún mi?
yoruba
female
18-29
phase 1
AI6WB
Oru ana ni won jo oko naa.
yoruba
male
6-17
phase 1
End of preview. Expand in Data Studio
README.md exists but content is empty.
Downloads last month
11