audio audioduration (s) 0.06 18.5 | speaker_id stringlengths 5 5 | text stringlengths 7 190 | language stringclasses 1
value | gender stringclasses 2
values | age_range stringclasses 3
values | phase stringclasses 2
values |
|---|---|---|---|---|---|---|
ZZ5EA | Aboki to ń ta índòmí ni ọkàn yẹn. | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
1SX0Y | Wálé ń gbèrò láti lọ sí ọjà ìdí òro láti ra ọ̀gẹ̀dẹ̀ àgbagbà lọ́la | yoruba | male | 18-29 | phase 1 | |
M70L7 | Odó àti ọmọdó ni a màa n fi gúnyán | yoruba | male | 18-29 | phase 1 | |
IF56O | Kílódé tí gbogbo àwọn oni káràkárà ó ṣí lónìí? | yoruba | female | 18-29 | phase 2 | |
ZHR4X | N̄ kò mọ ohun tí ìtàkurọ̀sọ ọlá yóò dá lé lórí. | yoruba | female | 18-29 | phase 2 | |
4YJ6B | Bàbá mi ṣàlàyé pé kò dára kí òwú aláǹtakùn ó máa bo ènìyàn lójú | yoruba | male | 6-17 | phase 1 | |
GL409 | Wọn máa báwa ra ẹ̀rọ amúwepọ̀ bọ̀ ni ọ̀la | yoruba | female | 6-17 | phase 1 | |
KY5I7 | Lílo omi tó lọ́wọ́rọ́ láti fi wẹ̀ dára fún ara | yoruba | female | 30-over | phase 2 | |
ZHR4X | Mò ń fún àwọn adìẹ ní ọkà-bàbà. | yoruba | female | 18-29 | phase 2 | |
18W0W | Gbogbo àwọn àdá tí àgbẹ̀ náà ń lò ni ó ti dógùn | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
SRYA7 | Ọlá ń ṣiṣẹ́ ọlọ́kadà | yoruba | female | 18-29 | phase 2 | |
RWUNS | “ Alákòóso ìbáṣepọ̀ ” ti lù ú ní jìbìtì. | yoruba | female | 30-over | phase 1 | |
DYBU5 | Gbigbe ikoko sere jẹ iṣe ti o wọpọ | yoruba | female | 30-over | phase 1 | |
M6SAQ | Ìṣirò ni bàbá mi kà. | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
FYM3V | Aburo baba mi yoo gbin igi giga si iwaju ile rẹ | yoruba | male | 30-over | phase 1 | |
G1RV1 | Èmi pẹ̀lú Bọlá ń jẹ́ fufu àti Ẹ̀fọ́ rírò | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
SKABL | Aworan jẹ aworan ti o tobi pupọ | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
XJ1AQ | Wuraola ń dáná nínú oru | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
MZLHM | Dídi àdìmọ́lẹ̀ wọ́pọ̀ láàárin àwọn obìnrin ilẹ̀ Yorùbá. | yoruba | male | 18-29 | phase 2 | |
7TZW9 | ṣe ayẹyẹ egúngún ẹ̀yọ̀ léwu ? | yoruba | male | 18-29 | phase 2 | |
VA1ZO | Tani ó sọ pé "Ewu ń bẹ lóko longe? | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
HZ67C | Awọn ẹgbẹ bii awọn ẹgbẹ masquerade ati awọn ẹgbẹ ijó awọn obinrin ṣe awọn ipa pataki ni titọju awọn aṣa aṣa | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
ZOL9F | Àwọ̀ ọsàn ní àwò àyànfẹ Kehinde | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
CRLYU | Oríṣiríṣi Ìjàpá ló wà. | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
3U6D4 | Ibo ni ìbúdókọ̀ ọkọ̀ ojú omi wà ní Ìbàdàn? | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
UPGFZ | Wọ́n ma gbé pọunpọ́ún náà wá sí sáìtì. | yoruba | male | 18-29 | phase 1 | |
Q6KV2 | A lọ sí ilé ìtura New Wine láti lọ gbafẹ́ | yoruba | female | 30-over | phase 2 | |
E9ZMS | O máa po bọ́tà náà pọ̀ mọ́ súgà náà! | yoruba | female | 6-17 | phase 1 | |
ZT805 | Ni oṣù ti n bọ, ilé àwọn abirùn yóò di kíkókuro ni ibi. | yoruba | female | 30-over | phase 1 | |
3N59Z | Olùkọ́ní náà fi kíláàsì sílẹ̀ tìbínú-tìbínú? | yoruba | male | 18-29 | phase 1 | |
YT0T2 | Àwọn ẹ̀dá ìtàn máa ń ní ojúṣe wọn. | yoruba | male | 18-29 | phase 2 | |
B5ONS | Ìyàwó ẹ̀gbọ́n mi fi ẹgbẹ̀ta Dọ́là ṣòfò | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
L88Q7 | Bẹ́ẹ̀ni, wúrà tó máa dán, á la iná kọjá. | yoruba | male | 30-over | phase 1 | |
MXTT9 | Kí ló dé tí ẹ fi gbá èjìká wọn? | yoruba | male | 30-over | phase 2 | |
HNSNF | Àwọn ọkùnrin àti obìnrin yóò gbá bọ́ọ̀lù papọ | yoruba | female | 18-29 | phase 2 | |
OASOS | Mórì búrọsi òdá tàn wà lọwọ kunle làná | yoruba | male | 30-over | phase 1 | |
ZLOOP | Àwọn awakọ̀ máa ń gba owó ẹrù na. | yoruba | male | 18-29 | phase 2 | |
ZLOOP | Ìbáraẹnisọ̀rọ̀ tó dánmọrán jẹ́ pàtàkì nínú gbogbo àjọṣepọ̀ àti ìgbéyàwó | yoruba | male | 18-29 | phase 2 | |
7TZW9 | Àìní ìmọ́tótó lè fa ifo | yoruba | male | 18-29 | phase 2 | |
VU1BN | Idije Ijakadi bẹrẹ ni aago meji alẹ | yoruba | male | 18-29 | phase 1 | |
B3Y8F | Olùkó sọ ìtàn òshun fún wón | yoruba | male | 30-over | phase 1 | |
EY2HD | Ọjọ́ wo ní baalú Ṣọlá máa lọ sí àbújá? | yoruba | male | 30-over | phase 1 | |
W8MQ2 | Akẹ́kọ̀ọ́ alábòójútó iṣẹ́ jẹ́ kí gbogbo akẹ́kọ̀ọ́ ṣiṣẹ́ lórí oko ilé-ìwé lánàá. | yoruba | female | 30-over | phase 2 | |
YT0T2 | Bamí ra tíkẹ̀ẹ̀ti ọkò òfurufú! | yoruba | male | 18-29 | phase 2 | |
L4CXW | Àlùfáà ìjọ mi rin ìrìn- àjò lọ sí Taxas lánàá. | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
FEESO | O ṣe awọn ipe nipasẹ FaceTime | yoruba | male | 18-29 | phase 1 | |
APQO2 | Kíkẹ́ ń mú ọbẹ̀ Báyọ̀ bọ̀ lọ́la | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
43FB0 | Njẹ ẹrọ orin DVD yẹn yóò ṣiṣẹ dáradára? | yoruba | female | 30-over | phase 2 | |
O0GW8 | Ṣé o ri lóri Facebook lánàá? | yoruba | male | 18-29 | phase 2 | |
PNUGF | Olùtọ́jú Ilé-ìgbọ̀nsẹ̀ máa wá lọ́sè tó ń bọ̀ | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
MXTT9 | Iná dára ní ìgboro. | yoruba | male | 30-over | phase 2 | |
O80JF | Mínísítà fún ètò ọkọ̀ òfurufú ti se ileri láti ṣe àtúnṣe pápákọ̀ òfurufú tó wà lékòó | yoruba | male | 30-over | phase 1 | |
K3KLM | Olùkọ́ ẹ̀kọ́-àwùjọ kò wá lónìí. | yoruba | male | 18-29 | phase 1 | |
0CXKQ | Kíni o fa ìjà láàrin yin? | yoruba | male | 30-over | phase 1 | |
HZM4L | Àdí àti epo pupa ní wọ́n fi ń bọ èṣù | yoruba | female | 30-over | phase 2 | |
CSMDP | A ti rí aṣọ dúdú àti aṣọ pupa lọ́rùn wọn rí. | yoruba | female | 18-29 | phase 2 | |
3O6YU | aré ọnà kankanfo abúlé yí tí kú . | yoruba | male | 18-29 | phase 1 | |
KY5I7 | Àwọn Oníṣègùn òyìnbó máà lo ọ̀pọ̀lọpọ̀ ọdún láti kẹ́kọ̀ọ́ ìmọ̀ ìṣègùn. | yoruba | female | 30-over | phase 2 | |
H51YJ | Bẹ́ẹ̀ni, àwọn ìwà àwùjọ aburú tó wọ́pọ̀ lónìí ni olè jíjà, irọ́ pípa àti panṣágà. | yoruba | male | 30-over | phase 1 | |
ELC7E | bánkì ìtọjú òwò gbígbà ní mó òwò ilé ìwé mí Si | yoruba | male | 30-over | phase 2 | |
IMYHK | Àwọn olùkọ́ máa ń kó ìwé ìkóninísé | yoruba | female | 6-17 | phase 1 | |
59INZ | Táyọ̀ o jẹ Sùpàgẹ́tì lálẹ́ | yoruba | male | 18-29 | phase 2 | |
PNUGF | Ìyá-àgbà mi sọ fún mi pé kò sí àwọn ilé-ìwé gíga aládáni láyé àtijọ́ | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
I8WRZ | Ọmọ íbò náà mọ bí wọ́n ṣe n kà àti bí wọ́n ṣe n kọ èdè yóòbá | yoruba | male | 18-29 | phase 1 | |
Q54MY | Mo máa ní kí ọmọbìnrin mi sọ ọ̀kan lára ọmọkùnrin rẹ̀ ní orúkọ mi. | yoruba | female | 18-29 | phase 2 | |
DD75D | ṣe awakọ náà tí mó ọtí? | yoruba | female | 30-over | phase 1 | |
8M4FR | Olùkọ́ kọ́ àwọn akẹ́kọ̀ọ́ ní Ọjọ́ Àìkú tó lọ. | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
GLELE | fífó eyín, ahón atí enú lòjojúmo mu kí o mó | yoruba | male | 18-29 | phase 1 | |
WN9Q2 | Ilé rè kún fún orísirísi àwon igi èso | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
4XT0F | Simi ma kọ́ bí wọ́n tí ń kọrin | yoruba | female | 18-29 | phase 2 | |
NNF2G | Ni ọjọ́ kini sí ọjọ́ keje oṣù kẹjọ gbogbo ọdún ni wọ́n máa ṣe àyájọ́ ọ̀sẹ̀ ìfọ́mọ lọ́yàn káríayé. | yoruba | female | 6-17 | phase 1 | |
MZLHM | Rárá, mi ò lọ sí Lọs Ánjẹ́lísì. | yoruba | male | 18-29 | phase 2 | |
9BO6Y | Kó àwọn òlè yẹ́n! | yoruba | male | 18-29 | phase 1 | |
O0GW8 | Ọ̀rẹ́ mi rà àkópọ́ dúdú ọ̀ṣun métà láti ojá lànà. | yoruba | male | 18-29 | phase 2 | |
543G7 | Tolú yóò pariwo mọ́ akọ̀wé ẹgbẹ́ rẹ̀ lórí bí ó bá wàhálà rẹ̀ | yoruba | female | 30-over | phase 1 | |
LA0Y9 | Ẹ̀gúsí olómi máa ń wù nínú yèpẹ̀ yarìn. | yoruba | female | 18-29 | phase 2 | |
VLZWS | Ọ́fíìsì ọ̀gá mi tẹ́lẹ̀ tó àpapọ̀ ọ́fíìsì tèmi àti tìrẹ. | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
HFDWN | Ibùdó ọkọ̀ ojú omi ṣe pàtàkì fún ìlọsíwájú àti ìdàgbàsókè ètò ọ̀rọ̀ ajé. | yoruba | male | 18-29 | phase 1 | |
Q6KV2 | Kíni wón fi n se ewédú? | yoruba | female | 30-over | phase 2 | |
S47FP | Ìyá àgbà wọn ṣẹ̀ṣẹ̀ kú | yoruba | male | 30-over | phase 1 | |
O0GW8 | Ilé ìtọ́jú ọpọlọ ni Jídé wà tẹ́lẹ̀ | yoruba | male | 18-29 | phase 2 | |
ZHR4X | Ẹran ìgbẹ́ ni mò ń yan. | yoruba | female | 18-29 | phase 2 | |
0F94V | Ẹ̀gẹ́ wà lára àwọn ohun tí wọ́n fi ń se ọtí bíà | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
4Z52Q | Ó wọ aṣọ tí kò bójú mú nínú eré náà | yoruba | male | 18-29 | phase 1 | |
59INZ | Owó náírà la gbàláyè fún ìtajà ní Nàìjíríà | yoruba | male | 18-29 | phase 2 | |
8K2XG | Ta ni ó ń súre fún ìkòkò náà? | yoruba | male | 18-29 | phase 1 | |
9BO6Y | Aremu ń ṣiṣẹ́ ní etí okun | yoruba | male | 18-29 | phase 1 | |
MVCK6 | Koroba ni máa ṣe tí mo bá ti tú irun yìí. | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
EG4SI | Àwọn dókítà ní kí Ade má jẹ súgà mọ́ kí ó sì máa lo òògùn àtọ̀gbẹ. | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
MZLHM | Ọlá máà ń ṣiṣẹ́ ní Yunifásítì Ìlọrin? | yoruba | male | 18-29 | phase 2 | |
OICUL | Wọ́n sábà máa ń dín tọkí àti adìẹ wọ́n sì tún máa ń bọ̀ ọ́. | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
OZCG2 | Gúdúgúdú jẹ ilu ibile tí awon Yoruba n lo | yoruba | female | 30-over | phase 2 | |
HH0CR | Awọn nọọsi ni awọn ọdun ti n bọ le ni awọn aṣọ | yoruba | female | 18-29 | phase 2 | |
LXBWP | Edé jẹ́ oúnjẹ odò | yoruba | female | 30-over | phase 1 | |
WH65Z | Ó gbọ́ tí àwọn olùkọ́ ń sọ̀rọ̀ lórí àwọn ohun èlò inú yàrá ìmọ̀ kẹ̀mísírì | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
AQ9WL | Mo má gba yàrá méjì ni ọ̀sẹ̀ tó ń bọ̀ | yoruba | female | 30-over | phase 1 | |
IF56O | Ní orile-ede china, èdè Chinese ní wón má sọ | yoruba | female | 18-29 | phase 2 | |
V0JI2 | Wo Ìyàrá òṣìṣẹ́ lọ! | yoruba | female | 6-17 | phase 1 | |
2WJTR | Wọ́n ma ṣègbéyàwó. | yoruba | female | 18-29 | phase 2 | |
QDMDD | Èmi ni mo ni aṣọ ọréńjì | yoruba | female | 18-29 | phase 1 |
End of preview. Expand in Data Studio
README.md exists but content is empty.
- Downloads last month
- 11