Dataset Viewer
Auto-converted to Parquet Duplicate
audio
audioduration (s)
0.06
23.6
speaker_id
stringlengths
5
5
text
stringlengths
8
184
language
stringclasses
1 value
gender
stringclasses
2 values
age_range
stringclasses
3 values
phase
stringclasses
2 values
2SCF8
Ọ̀pọ̀ aṣọ ni wọ́n ṣé láti ẹ̀gbọn òwú
yoruba
female
18-29
phase 2
ZLJPP
Ile iṣere atijọ ti duro ipalọlọ ati eruku
yoruba
female
30-over
phase 1
1EORU
Owerri ni wọ́n gbé ọmọ náà lọ.
yoruba
female
30-over
phase 1
KSYPO
Àìní ẹni kankan lọ sọ Ẹniìtàn di olè tó ń jí oúnjẹ kiri àdúgbò
yoruba
female
18-29
phase 2
C0ZXJ
wọ́n ṣe ẹ̀wà ní ibi ìkómọ àwọn Ìbejì náà bíi orò ìbejì wọn
yoruba
female
18-29
phase 1
KSYPO
Èkúté ń jẹ oúnjẹ rẹ
yoruba
female
18-29
phase 2
ZJ3AR
Mi grandfather toothpaste ni o ni a minty lenu
yoruba
female
18-29
phase 1
CWHE5
Ènìyàn mẹ́rin ni a tí pàdánù látàri í òògùn olóró kokénìí.
yoruba
male
18-29
phase 1
WMEEI
Ìjà omi ṣẹlẹ̀ ní àdúgbò náà
yoruba
male
30-over
phase 1
KY5I7
Ara igi ọ̀pẹ ní a tí n rí ẹmu.
yoruba
female
30-over
phase 2
HZM4L
Ó máa lọ sí suwimi púùlù.
yoruba
female
30-over
phase 2
HNSNF
Ọjọ́ àìkú ni àwọn kìrìtíẹ́nì máa ń lọ sí ilé-ìjọsìn
yoruba
female
18-29
phase 2
NGK6O
Òróró ni a lè fi dín ẹyin
yoruba
male
6-17
phase 1
4ANQN
Ó pàdánù àwọn òbí rẹ̀ nì wọ́n se mú lọ sí ilé ìtọ́jú àwọn ọmọ aláìlóbí.
yoruba
female
30-over
phase 1
HPTGN
Fún mi ní ẹ̀ẹ́dẹ́gbẹ̀ta náírà!
yoruba
female
18-29
phase 2
E9ZMS
Ohun ọ̀gbìn oko rẹ kò ṣe dáadáa nítorí pé o kò fi àlàfo fún wọn dáadáa.
yoruba
female
6-17
phase 1
5KCR8
Awakọ̀ ọkọ̀ ojú omi sọ fún wípé kò gbọ́dọ̀ kúrò lórí pápá ìgbafẹ́ ọkọ̀ ojú omi náà
yoruba
female
18-29
phase 1
UNW13
Wá gba oògùn ìtọ̀ ṣúgà yìí lọ́wọ́ mi!
yoruba
male
18-29
phase 1
SRYA7
Adẹ́lẹ̀yẹ̀ yóò lọ sí ọjà láti rá àwọn ọhun ẹ̀lọ́ itánná.
yoruba
female
18-29
phase 2
XU8RR
Ọ̀pọ̀ àwọn aláìní iṣẹ́ tó jẹ́ ọ̀dọ́ ni wón jẹ́ adérùbànìyàn.
yoruba
male
30-over
phase 1
5C64C
Kainkain kíríkẹ́tì máa ń pariwo
yoruba
female
18-29
phase 1
2WJTR
Ṣo rànán lọ́wọ́?
yoruba
female
18-29
phase 2
3ZVRE
Wọn tí kọ́ yàrá ìkàwé tuntun sí ọgbà ilé ẹ̀kọ́ wá.
yoruba
female
18-29
phase 1
8CGWQ
Ṣé igbákejì ọ̀gá ilé-ìwé náà n sọ̀rọ̀ dípò ọ̀gá ilé-ìwé?
yoruba
female
18-29
phase 1
M5WGD
Bẹ́ẹ̀ni, mo máa jẹ́ moi moi àti búrẹ́dì.
yoruba
female
30-over
phase 1
BCVY1
Ṣo lè ṣe àkàrà ọ̀yìnbó?
yoruba
male
30-over
phase 1
24ZOQ
Ó fẹ̀yìntì gẹ́gẹ́ bí òṣìṣẹ́ ìjọba ní ọ̀sẹ̀ tó kọjá
yoruba
female
18-29
phase 1
YVQQZ
Ṣáwà wà fún ìwẹ̀.
yoruba
female
30-over
phase 1
W7YLH
Gbogbo nǹkan abẹ̀mí ló máa kú
yoruba
female
18-29
phase 1
Q6KV2
Ẹ kú ìrìn, ṣe kò rẹ ara?
yoruba
female
30-over
phase 2
2WJTR
Iro, buba àti gèlè wọ́pọ̀ láàárín àwọn ọmọbìnrin ilẹ̀ Yorùbá.
yoruba
female
18-29
phase 2
92JZ4
Awọn olujọsin IFA yoo wọ awọn aṣọ funfun .
yoruba
female
30-over
phase 1
HPTGN
Àwọn ọmọ ilé ìwé máa ń pè fún èsì wọn ní record unit.
yoruba
female
18-29
phase 2
V0AVQ
Bọlá tí ṣe ìdánilẹ̀kọ̀ fún wa lori awọn ewébẹ̀ àti èso.
yoruba
female
18-29
phase 1
W8MQ2
Eré ìje náà, tí ó ń wáyé lọ́dọọdún, máa ń fa àwọn eléré-ìdárayá láti àwọn agbègbè tó wà nítòsí.
yoruba
female
30-over
phase 2
GTI5O
Ìlé õtí jé ìbí tí èyan lé jòkò mú õtí
yoruba
male
18-29
phase 1
MXTT9
Táyọ̀ máa ń wá sí ilé-ìwòsàn ní lójoojúmọ́ láti wá wo ìyá rẹ̀ tó ṣàìsàn.
yoruba
male
30-over
phase 2
OU692
Fọ aṣọ ọmọ ẹ. Má kó wọn jọ!
yoruba
female
18-29
phase 1
77Y1D
Mo rí igi obì kan ní pápá ìṣeré.
yoruba
female
6-17
phase 1
V6MKF
Ìròyìn máa ń wàlórí pépà
yoruba
female
18-29
phase 2
92JZ4
Máa ra oúnjẹ ní búkà ní ọjọ ajé
yoruba
female
30-over
phase 1
ZLOOP
Ṣé sọ́kẹ́ẹ̀tì yẹn bàjẹ́ lánàá.?
yoruba
male
18-29
phase 2
OJ2WU
Ọ̀pọ̀ obìnrin ni wọ́n ti lóyún ọmọ rí.
yoruba
male
18-29
phase 1
HIZA4
Ọdún tó ń bọ̀ ni ìjọba àpapọ̀ yóò fọwọ́ sí ẹ̀ka ẹ̀kọ́ ìmọ̀ ẹ̀dá-èdè
yoruba
female
18-29
phase 1
KGY1J
Awakọ̀ náà yí padà, ó sì darí padà sí apá Àríwá.
yoruba
male
30-over
phase 1
645HA
Màá bèrè bóyá ilé-ìtura náà ni bẹ́ẹ̀dì míì.
yoruba
male
18-29
phase 1
SBLJM
Ẹ̀sùn mẹ́sàn-án ni wọ́n fi kàn wọ́n.
yoruba
male
18-29
phase 1
O8RIH
Ọdún 1960 ni Nàìjíríà bó lówó ìṣèjọba amúnisìn.
yoruba
male
30-over
phase 1
VBGAM
Ile-ikawe naa ko ṣii.
yoruba
female
6-17
phase 1
HNSNF
Erin ni ọdẹ náà pa lóṣù tó kọjá.
yoruba
female
18-29
phase 2
ERKIJ
Njé wón ní ilé adagbe to rẹwà kí agbami to sẹlẹ ?
yoruba
male
30-over
phase 1
OZCG2
orukọ re jẹ bísòla, àdùké atí kemísólá.
yoruba
female
30-over
phase 2
7TZW9
Orò mọ̀lẹ́bí kan ni kí bàbá bá ìyàwó ọmọ rẹ sùn lálẹ́ ìgbéyàwó
yoruba
male
18-29
phase 2
HZM4L
Béèni wón sìn ló Máíkírósíkópù.
yoruba
female
30-over
phase 2
O0GW8
Joke so fun mi nipa itan alarinrin madam koi koi, iberu ba mi pupo.
yoruba
male
18-29
phase 2
V6MKF
Ibi ìṣeré àṣà máa ń fi àṣà àti ìṣe hàn
yoruba
female
18-29
phase 2
MXTT9
Àlá Adé ni láti di reporter.
yoruba
male
30-over
phase 2
05HN6
Ta ni ó ń lo Facebook?
yoruba
male
18-29
phase 1
IXP4M
Ebuka ṣe akiyesi ṣiṣẹda eto incubator kan fun awọn alakoso iṣowo dagba
yoruba
male
18-29
phase 1
M8U45
Gíráfítìn wà fún àwọn àgbẹ̀ tó mọ iṣẹ́.
yoruba
female
30-over
phase 1
Z8MF7
Igi mòríńgà ń bẹ ní ẹ̀yìnkùlé mi.
yoruba
female
18-29
phase 1
II8KP
Báàgì jẹ́ ohun tí a fi ń gbé ẹrù
yoruba
female
18-29
phase 2
IGDIT
Wọ́n fí ápú àti ọbẹ̀ bàùngá bọ́ wa níbí ìnáwó mọ̀-mi-mọ̀-ọ́ ọmọ-ẹ̀gbọ́n bàbá mi
yoruba
male
18-29
phase 1
NX2C5
Awọn akọle ti o wa ni agbegbe pẹlu "Onwa-na-etili-ora," eyi ti o ṣe afihan olori ti a bọwọ fun
yoruba
male
18-29
phase 1
YT0T2
Alade ó ṣe ìgbéyàwó ní òpin ọ̀sẹ̀
yoruba
male
18-29
phase 2
VUV3K
Mo ríi ní Ófììsì Ọ̀gá àgbà fún ẹ̀ka ẹ̀kọ́
yoruba
male
18-29
phase 1
RD72Z
Mo rán Sadé ni Gabbage ni ana
yoruba
male
18-29
phase 1
MXTT9
Yàrá ìkàwé wà fún oríṣiríṣi ìpele ní ilé ìwé alákọ̀ọ́bẹ̀rẹ̀ .
yoruba
male
30-over
phase 2
64E8A
Mo sọ fún Tunde pé kí o lọ rí Dókítà ní àná
yoruba
male
18-29
phase 1
1ULWV
Awọn ọdọ ti n sín orilẹ-ède yóò gbà aṣọ ìṣọ̀kan
yoruba
male
30-over
phase 1
VQI6V
Wọ́n lè fi síkúù ká ohun ọ̀gbìn.
yoruba
female
18-29
phase 1
QTH4S
Bàbá ní olórí ilé.
yoruba
female
6-17
phase 1
PVCEO
Mo fẹ́ràn láti má jè ọgẹdẹ nitoripe o da lara
yoruba
female
18-29
phase 1
MXTT9
Ẹ̀sin krìstẹ́nì fi ara mọ́ ìdílé oníyàwò kan.
yoruba
male
30-over
phase 2
S15C9
Bí púpọ̀ nínú àwọn ọ̀dọ́ òní kò bá níwà ọmọlúwàbí, báwo ni tàwọn ọdún tó ń bọ̀ yóò ṣe jẹ́.
yoruba
female
18-29
phase 1
G1ERL
Arákùnrin náà n'ifẹ láti gbádùn pẹlú àwọn ọmọ rẹ nínú ọgbà iṣere ìyanu.
yoruba
female
30-over
phase 1
CWMW8
Ṣé o kò rí ákítọ̀ náà ní àná?
yoruba
male
18-29
phase 1
RG8GO
Rárá, àwọn baba nlá rẹ̀ ni.
yoruba
female
18-29
phase 1
YT0T2
Wàrà didi àti àwọn oúnjẹ ijekuje ni coldstone máa ń tà.
yoruba
male
18-29
phase 2
33QY9
Ìdíkọ̀ ni mọ́tọ̀ tí máa ń dúró.
yoruba
female
18-29
phase 1
PYFIU
Títa owó lórí eré ìdárayá kò dára fún ìwà rere.
yoruba
female
18-29
phase 1
0KQA0
Mo lọ ri Díìnì ẹ̀ka ẹ̀kọ́ áàtì ni àná
yoruba
female
6-17
phase 1
43FB0
Bẹ́ẹ̀ni, mà á yẹ radiétọ̀ wò.
yoruba
female
30-over
phase 2
5O9PO
Kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ náà sáré.
yoruba
male
18-29
phase 1
MYLYJ
Ẹka igbasilẹ ntọju igbasilẹ ti gbógbó ọrọ tí ìlé-ìwé náá
yoruba
female
30-over
phase 1
2OXGE
Ọ̀pọ̀lọpọ̀ ọkọ̀ ni ó wà ní ibùdókọ̀.
yoruba
female
18-29
phase 1
3U6D4
Níbò ní à tí pàdé láti jírórò lórí ìgbéyàwó rẹ̀?
yoruba
female
18-29
phase 1
ZT805
Títí oṣù tó ń bọ̀ oyún ìyàwó máa wà ní ìpele kẹta
yoruba
female
30-over
phase 1
0CXKQ
Ilu wo ni Olóògbé ti wa?
yoruba
male
30-over
phase 1
EA51P
Àwọn àgbẹ̀ kan máa ń gbin àwọn ẹ̀fọ́ nìkan.
yoruba
female
30-over
phase 1
OVFI5
Lọ ra óúnjẹ wá ní kàńtìnì!
yoruba
female
18-29
phase 2
M4J0U
Ibi eré Ìdárayá máa n dùn
yoruba
female
30-over
phase 1
C36U6
Gbẹ́nàgbẹ́nà náà ń tà jig saw
yoruba
female
6-17
phase 1
AHT53
Àti mùsùlùmí, àti onígbàgbọ́ ló máa lọ ìsìnkú ọba yìí
yoruba
male
18-29
phase 1
MXTT9
Lára èso ni wọ́n ti ń yọ juice
yoruba
male
30-over
phase 2
VUGDK
Màá síkípù ni ọ̀lá kí ara mi lè jí pépé.
yoruba
female
30-over
phase 1
KSYPO
Ọgọ́rùn-ún náírà ni gálà mi.
yoruba
female
18-29
phase 2
HNSNF
Adarí obìnrin yóò pe Irun tuntun fún àwọn obìnrin.
yoruba
female
18-29
phase 2
BN1ZC
Àwọn Ọmọ n ṣeré lábé igi osè
yoruba
female
18-29
phase 2
SWTTM
Káfíntà nlo ounwọ̀nkan láti fi wọn pákó.
yoruba
male
18-29
phase 1
End of preview. Expand in Data Studio
README.md exists but content is empty.
Downloads last month
12