Dataset Viewer
Auto-converted to Parquet Duplicate
audio
audioduration (s)
0.06
23.6
speaker_id
stringlengths
5
5
text
stringlengths
2
168
language
stringclasses
1 value
gender
stringclasses
2 values
age_range
stringclasses
3 values
phase
stringclasses
2 values
LXBWP
Ṣẹ̀dá igun gangan nípa lílo béfẹ́ẹ̀lì sisun
yoruba
female
30-over
phase 1
MZLHM
Ọlá Obi ṣì wà ní ìparun nígbà àwọn ipò tí ó le.
yoruba
male
18-29
phase 2
CXZOR
Ìtàná gbogbo inú ilé wà lórí àpótí iná.
yoruba
male
30-over
phase 1
OQZKZ
èrò o pọ ninu oko yí!
yoruba
female
6-17
phase 1
TUJLE
Rárá, ìyá rẹ̀ lọ sí Canada.
yoruba
female
18-29
phase 1
38CRD
Ẹja makarẹli ni a mọ sí ẹja titúsí ní Nàìjíríà.
yoruba
female
18-29
phase 1
HH0CR
Awọn eniyan sọ pe corporal kọ ile nla kan ni abule rẹ
yoruba
male
18-29
phase 2
ZLOOP
Gbogbo ilé ni o ni ilẹkùn.
yoruba
male
18-29
phase 2
ZQUY1
Shùwákà jẹ́ ewé tó n lò fún ọgbẹ́ ọkàn
yoruba
female
30-over
phase 1
OZCG2
Ṣé o rí ìyarun mi?
yoruba
female
30-over
phase 2
GHP05
Wọ́n máa ń lo àwọn kẹ́ẹ́tẹu fi gbomi ka'na fún mímu.
yoruba
male
18-29
phase 1
OR57E
Ǹjẹ́ ó fẹ́ràn gẹ́ṣà nínú oúnjẹ ẹ
yoruba
female
18-29
phase 1
HNSNF
Ajá náà ń rọ̀bí
yoruba
female
18-29
phase 2
HNSNF
Bíríkìlà náà yóò kọ́ ṣọ́ọ́bù pẹ̀lú àpò sìmẹ́ńtì kan.
yoruba
female
18-29
phase 2
MZLHM
Paul má pààrọ̀ Táyà mọ́tò rẹ
yoruba
male
18-29
phase 2
FTDAG
Jẹ́ ẹ̀rí gẹ́gẹ́ bíi o ti búra
yoruba
female
18-29
phase 1
QQ19Q
Mo fẹ́ lọ ra bentiro fun katakata
yoruba
female
18-29
phase 1
LGUC3
Adéṣẹwà jẹ́ orúkọ obìnrin.
yoruba
female
18-29
phase 1
5TLPT
Ṣé o máa bẹ̀rẹ̀ sini ta oògùn ara ríro?
yoruba
male
18-29
phase 1
YT0T2
Àpẹẹre nìkan ni àwọn ọmọdé yóò fi kọ nǹkan.
yoruba
male
18-29
phase 2
UYYNZ
Apulu je eso to dara fun ilere inu
yoruba
male
18-29
phase 1
TF61S
Ṣé o tí dín dòdò náà?
yoruba
male
30-over
phase 1
22E62
Lọ ra ọṣẹ ìṣerun wá fún mi.
yoruba
female
6-17
phase 1
59INZ
Mà á lọ gba tírè mi làárọ̀
yoruba
male
18-29
phase 2
MUC0G
Òun ni ìyálóde tẹ́lẹ̀
yoruba
female
30-over
phase 1
2CUT1
Ẹ́ńjì jẹ́ ẹ̀yà ara mọ́tò tí ó ṣe pàtàkì jù
yoruba
female
30-over
phase 1
V6MKF
Kíni o rá nígbà tí o lọ sí Àbújà?
yoruba
female
18-29
phase 2
V8VTJ
Ṣé ó máa gẹ irun rẹ lójoojúmọ́?
yoruba
female
30-over
phase 1
6LHU5
Awọn apakan ninu ile-iṣẹ atẹjade kan pẹlu olootu, apẹrẹ, titẹjade, ati pinpin ni awọn iṣẹ iṣaaju
yoruba
female
18-29
phase 1
O4S93
Ṣé ó máa fi owó pamọ́ lójoojúmọ́?
yoruba
female
18-29
phase 1
ZLOOP
Má fi àtẹ̀jíṣẹ́ kankan ránṣẹ́ sí mi lórí Facebook
yoruba
male
18-29
phase 2
U8PZ4
Radiator náà gbiná
yoruba
female
18-29
phase 1
SRYA7
Àyìndẹ́ kò sí nínú àkọsílẹ̀ náà
yoruba
female
18-29
phase 2
M97JE
Ehoro jẹ́ ẹranko tó yára fáfá
yoruba
female
30-over
phase 1
KSWZ5
Gbogbo ọmọdé máa ń tẹ́tí nígbà tí àgbà bá ń pa àlọ́.
yoruba
female
18-29
phase 1
2OU1D
Ṣé ìwọ kọ́ni awakọ̀ ọkọ̀ ojú omi yìí tẹ́lẹ̀ ni?
yoruba
male
18-29
phase 1
QQ19Q
Mo fẹ́ jẹ ewúro
yoruba
female
18-29
phase 1
ZD9SH
Àbúrò mú obinrin yóò sùn sórí ibùsùn mi lálẹ́ yìí.
yoruba
female
6-17
phase 1
LPWNY
Ó ma nu ọ́fìsì olú àdínì lọ́la.
yoruba
male
30-over
phase 1
ZLOOP
Ǹjẹ́ o mọ bóyá alágbẹ̀dẹ le rọ ìkòkò onírin?
yoruba
male
18-29
phase 2
1YOTL
Ìgbà kan wà tí orílẹ̀-èdè Nàìjíríà n ṣé ìṣèjọba asọ̀fin
yoruba
female
18-29
phase 1
HNSNF
Iṣẹ́ àjùmọ̀ṣe náà yóò nílò ìfọ́wọ́sọwọ́pọ̀.
yoruba
female
18-29
phase 2
K0YIP
Ṣé o lè ìsàrẹ́ ní ọlá?
yoruba
male
18-29
phase 1
VUGDK
Mo máa bu ọ̀wọ̀ fún ẹni tó tọ́ sí.
yoruba
female
30-over
phase 1
674MN
Chicken republic ni ilé ìtajà ogójì ni Ìpínlẹ̀ Èkó
yoruba
male
18-29
phase 1
FO18W
Ẹyẹ iwo ti sába lé ẹyin.
yoruba
female
18-29
phase 1
HNSNF
Ọjà náà gbé ìwọ̀n gan-an.
yoruba
female
18-29
phase 2
ZHR4X
Mo ní ilé tí wọ́n tí ń ta ìwé
yoruba
female
18-29
phase 2
LRMKP
Ogun àwítẹ́lẹ̀ kìí pa arọ tó bá gbọ́n.
yoruba
male
30-over
phase 1
Q6KV2
Wọ́n yóò gbé ìwé ìròyìn kan jáde lóṣù tó ń bọ̀
yoruba
female
30-over
phase 2
59INZ
Bẹ́ẹ̀ni, ó máa gbé ẹbọ náà sóríta
yoruba
male
18-29
phase 2
K74O6
Àwọn òṣìṣẹ́ tó wà ní ibùdó ọkọ̀ ojú omi máa ń wo aṣọ kan náà fún ìdánimọ̀
yoruba
male
18-29
phase 1
HXQUJ
Ọdún mẹ́rin sẹ́yìn ni mo wọ Fáṣítì ìlú Èkó
yoruba
male
18-29
phase 1
2WJTR
Apá òsì ni ìjókòó awakọ̀ máa ń wà.
yoruba
female
18-29
phase 2
MXTT9
Táyọ̀ sọ pé wọ́n fún òun ní abẹ́rẹ́ ní alẹ́ àná.
yoruba
male
30-over
phase 2
W8MQ2
Olùkọ́ náà yóò kọ́ ẹgbẹ̀rún lè ní eejidinlaadọrun akẹ́kọ̀ọ́
yoruba
female
30-over
phase 2
WF0J4
Ṣo fi ṣọ́lù sínú kábínẹ̀tì ọmọwọ́ ?
yoruba
male
18-29
phase 1
CSMDP
Àdìsá mu àgbo gbígbóná náà.
yoruba
female
18-29
phase 2
V0JI2
Gbogbo ilé-ìwé máa n gba asọ́bodè fún ètò ààbò .
yoruba
female
6-17
phase 1
U5JZU
Igi ni a fi ń kan ilé
yoruba
female
30-over
phase 1
ZAFUM
Wọn ti sọ́ọ̀sì
yoruba
female
18-29
phase 1
J1KV0
Ọ̀pọ̀ àwọn ọmọge ló fẹ́ràn písà.
yoruba
male
30-over
phase 1
7Q08A
Iye owo ilẹ ni awọn ilu gbowolori
yoruba
female
30-over
phase 1
9BSXQ
Mo ma ahéré alàmọ̀.
yoruba
female
30-over
phase 1
6C8VN
Oko ile-iwe gbin orisirisi ẹfọ ati kọ awọn ọmọ ile-iwe nipa iṣẹ-ogbin
yoruba
female
18-29
phase 1
8SJ3J
Ṣètò ìpàdé ìtàn ní alẹ́ yìí lábẹ́ ìmọ́lẹ̀ òṣùpá fún gbogbo ọjọ́ orí.
yoruba
female
18-29
phase 1
VKW4W
A gba ojú òpópónà márosẹ̀ dé ilé.
yoruba
male
18-29
phase 1
YEI1F
Àwọn mìíràn yóò kọ́ ọ́fíísì.
yoruba
male
18-29
phase 1
XLLMX
Mo ni dùndún yẹn.
yoruba
male
6-17
phase 1
KQWBJ
Oja Bodija ni Ilu Ibadan, jẹ apẹẹrẹ ti awọn ọja eso ati ẹfọ.
yoruba
female
18-29
phase 1
MF6K9
Ipò ológun ni Major tó ju ipò Captain lọ.
yoruba
female
30-over
phase 1
0FORY
Kó̩lá kò rís̩é̩ akò̩wé náà gbà
yoruba
female
18-29
phase 1
LOISH
Olùkọ́ ìmọ̀-nípa-ẹ̀kọ́ ilé yóò kọ́ àwọn akẹ́kọ̀ọ́ bí wọ́n ṣe ń ṣe àkàrà-òyìbó.
yoruba
female
18-29
phase 1
HZM4L
Ènìyàn lè gbà yàrá kalẹ ni ilé ìtura
yoruba
female
30-over
phase 2
W8TSW
lali, awọ adayeba ti o wa lati inu ọgbin lali, jẹ lilo aṣa fun aworan ara igba diẹ ati awọ irun
yoruba
female
30-over
phase 1
KY5I7
Mo ti dé Ojúbọ ọya rí.
yoruba
female
30-over
phase 2
MWJC3
Ọmọbinrin naa ni arun kan.
yoruba
female
18-29
phase 1
II8KP
Won má ń lo èédú láti fi ya àwòrán
yoruba
female
18-29
phase 2
MGWAM
Ìtọ̀ju post Natal ni yo ri dájú pé ìyá àti ọmọ náà wà ní ìlera
yoruba
female
18-29
phase 2
43FB0
Ṣo ma tẹ́lè mi lọ wọ fíìmù "The tribe called Judah" pẹ̀lú mi?
yoruba
female
30-over
phase 2
W8MQ2
Ìsọwọ́rẹ́rìn ọmọdé nígbà tí wọ́n bá ń bá a ṣeré má ń mú inú ẹni dùn
yoruba
female
30-over
phase 2
MO1CL
Mi ò jí owó náà.
yoruba
male
30-over
phase 1
SESAF
Àlùfáà náà yóò dári ìjọ náà láti jọ́sìn ní ìrọ̀lẹ́ òní
yoruba
female
18-29
phase 1
HH0CR
Àwọn ará Òndó àti Èkìtì ló fẹ́ràn Iyán jù.
yoruba
male
18-29
phase 2
Q54MY
Juwon yóò rí ìpaniláyà ni ilé ìwé yén.
yoruba
female
18-29
phase 2
4FR3A
Òfún ní a fí yan àkàrà òyìnbó náà.
yoruba
female
30-over
phase 1
2W1XG
Awọn ọmọ óbìrín yèn ṣéré tẹntẹn
yoruba
male
30-over
phase 1
OZCG2
ìgbéyàwó akọkọ yóò ṣo obinrin kan mọ ọkunrin lapákán titi ti wọn yóò fí ṣe ìgbéyàwó ní kikún.
yoruba
female
30-over
phase 2
LJP8O
Ìwé ìyànyàn kò ní pẹ́ jáde
yoruba
male
18-29
phase 1
SJXWQ
Ilé ìjósìn ni àwọn ẹlẹ́sìn krìstẹ́nì máa tí ń jọ́sìn.
yoruba
female
6-17
phase 1
CGQWW
Oun yoo gbẹ eran malu ni ọla
yoruba
female
18-29
phase 1
SX9RB
Ṣé ìwọ lo ni aṣọ ìdábòbò?
yoruba
male
18-29
phase 1
IXP4M
Adebayor oluyọọda ni ile orukan, pese itọju ati atilẹyin si awọn ọmọde ti o ni ipalara
yoruba
male
18-29
phase 1
GL409
Wọ́n máa ṣe èkuru fún ọdún àwọn ìbejì tí ó ń bọ̀.
yoruba
female
6-17
phase 1
XJ0U9
Alukoro náà máa ṣojú ilé iṣẹ́ náà.
yoruba
female
18-29
phase 1
V6MKF
O daju pé ewé dóńgóyárò máa wà lára ohun tí wọ́n fi ń ṣe ìwòsàn àrùn àwọ̀ ara
yoruba
female
18-29
phase 2
POPB8
Njé àlọ́ àpagbè kán ní ìyá àgbà sọfún wá?
yoruba
male
18-29
phase 1
5C64C
Rárá, labalábá ò ní bù ó jẹ
yoruba
female
18-29
phase 1
Q7FW1
Mo ti ra ìyẹ̀fun tí o fẹ́ lò fún àkàrà oyinbo.
yoruba
female
18-29
phase 2
MGWAM
Rí i dájú pé o lọ fún antinátà
yoruba
female
18-29
phase 2
End of preview. Expand in Data Studio
README.md exists but content is empty.
Downloads last month
61