audio audioduration (s) 0.06 20.6 | speaker_id stringlengths 5 5 | text stringlengths 8 174 | language stringclasses 1
value | gender stringclasses 2
values | age_range stringclasses 3
values | phase stringclasses 2
values |
|---|---|---|---|---|---|---|
2WJTR | Ọmọ náà ja itọ́ lẹ́nu | yoruba | female | 18-29 | phase 2 | |
K3VHU | Ìnákí tí o̩de̩ yìí lọ bá yìí ni á s̩ekú pa á. | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
OTSUA | Ẹka ti Eda Eniyan ṣawari awọn koko-ọrọ bii Itan-akọọlẹ, Imọye, ati Awọn Ede | yoruba | female | 30-over | phase 1 | |
W1S8P | Ǹjẹ́ o mọ pé olùkọ́bìnrin ló jẹ oúnjẹ ọmọ rẹ lánàá? | yoruba | male | 18-29 | phase 1 | |
MO1CL | Mo fẹ́ lọ sí sinimá. | yoruba | male | 30-over | phase 1 | |
W8MQ2 | Ọkunrin naa ṣalaye awọn anfani ti oorun didara | yoruba | female | 30-over | phase 2 | |
II8KP | Àyìnkẹ́ fẹ́ràn láti máa da ìyá a rẹ̀ láàmú kí ó tó sùn | yoruba | female | 18-29 | phase 2 | |
2EBXD | Àwọn ọmọdé máa ń lọ sí ọgbà-ìṣeré nígbà ìsìnmi. | yoruba | female | 30-over | phase 1 | |
7D9CW | Diẹ ninu awọn èdè Nàìjíríà, bí èdè Yorùbá, ni awọn aṣa atọwọdọwọ | yoruba | male | 30-over | phase 1 | |
Z4FYP | Àwọn akẹ́kọ̀ọ kórìíra ìṣe ìṣirò | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
HH0CR | Àádọ́jọ náírà lè fẹ́ ìyàwó láyé àtijọ́ | yoruba | male | 18-29 | phase 2 | |
P10VD | Ẹ́ka ẹ̀kọ́ ní ọgbà OAU má a ń wọ asọ aláwọ̀ omi aró àti dúdú gẹ́gẹ́ bíi aṣọ ẹgbẹ́jọdá wọn | yoruba | female | 6-17 | phase 1 | |
Q54MY | Mo ti lọ fún ìtọ́jú àìsàn kíndìnrín | yoruba | female | 18-29 | phase 2 | |
POPB8 | njé Habib ń Tèlé wón ló sì ọgbà omi bayí? | yoruba | male | 18-29 | phase 1 | |
0X4MG | Alákòóso ilé ìwé girama ni a mò̩ sí ò̩gá ilé ìwé | yoruba | female | 30-over | phase 1 | |
ELC7E | Ábò ni ibi ti áwòn òkòójùómì má n gúnlé si lébùté | yoruba | male | 30-over | phase 2 | |
L88Q7 | Olùsọ́-àgùntàn tàbí Àlùfáà ni olórí ìjọ; àfáà tàbí ìmáàmú ní olórí mọsálásí. | yoruba | male | 30-over | phase 1 | |
7TZW9 | Aṣọ́gbà ni ó máa ń ṣe ìtọ́jú ọgbà | yoruba | male | 18-29 | phase 2 | |
LA0Y9 | Ìdánilẹ́kọ̀ọ́ kan wà fún àwọn ajábọ̀ ìròyìn. | yoruba | female | 18-29 | phase 2 | |
LG0JN | S̩é ò̩ò̩nì àti àǹtà kò jo̩ra wo̩n? | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
VMLSZ | Ni òye ohun kí o tó ṣe ohun. | yoruba | male | 30-over | phase 1 | |
LA0Y9 | Àwọn ààrẹ àná kọ̀ọ̀kan sì wà láàyè. | yoruba | female | 18-29 | phase 2 | |
0UH34 | Wọn ma ń já ewé mòríngà fún ìṣaralóore rẹ̀ | yoruba | female | 30-over | phase 1 | |
Z4PW2 | Bẹ́ẹ̀ni, mo tẹríba fún ọmọ ọba náà | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
ELC7E | Soji n tá igbó áti kólórádó lòwò | yoruba | male | 30-over | phase 2 | |
WQWJK | Bẹ́ẹ̀ni, mo ti gbìyànjú láti dín àgbàdo rí. | yoruba | male | 18-29 | phase 1 | |
JT49F | Ibùdó òkun wo ni ó máa kọ́ àwọn ọmọ náà máa lọ fún ìrírí. | yoruba | male | 18-29 | phase 1 | |
TUCTY | Ohun burúkú jí ṣíṣẹ́ èpè fún àwọn ènìyàn. | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
YH50Q | Mo to ìwé mi dáradára sínú ìwé ìpamọ́ mi gẹ́gẹ́bí ìyá mi ṣe sọ. | yoruba | male | 30-over | phase 1 | |
PCI9Z | Bẹ́ẹ̀ni, mo mọ̀ pé wọn máa ń lo owó ẹyọ gẹ́gẹ́ bí ohun rírà àti títà ní ayé àtijọ́. | yoruba | female | 6-17 | phase 1 | |
HH0CR | Abanirojọ máa ń fi ẹ̀sùn kan ènìyàn nílé ẹjọ́ | yoruba | male | 18-29 | phase 2 | |
2SCF8 | Aṣọ ilé ìwé mi rẹwà | yoruba | female | 18-29 | phase 2 | |
SRYA7 | Adé yóò ṣe tákò fún Olú. | yoruba | female | 18-29 | phase 2 | |
NEII5 | Bàlùwẹ̀ wa wà ní ẹ̀yìnkùlé | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
BN1ZC | Ọ̀dùnkún dùn lọpọlọpọ, ó sì da fún àwọn tó ní Àtọ̀gbẹ. | yoruba | female | 18-29 | phase 2 | |
S5Z0E | Rárá, mi ò lọ sí ilé ìwé ìmọ̀ ẹ̀kọ́ | yoruba | female | 6-17 | phase 1 | |
E9GQY | Olú yóò lọ sí ibùdó ọkọ̀ láàárọ̀. | yoruba | male | 30-over | phase 1 | |
TLXES | Inú ilé olórogún ni a bí mi sí. | yoruba | male | 30-over | phase 1 | |
OZCG2 | Àwọn babaláwo máà ń bá àwọn ènìyàn ṣe ògùn owó. | yoruba | female | 30-over | phase 2 | |
0W8O0 | Ewé àti egbò ni àwọn baba wa fi kojú àwọn àrùn ní ìgbà ayé wọn. | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
ZLOOP | Oríṣiríṣi ìwé la lè rí ní yàrá ìkàwé. | yoruba | male | 18-29 | phase 2 | |
ETBN5 | Akọ̀wé, lọ mú àwọn ìwé ìkọpámọ́ tí ọ̀sẹ̀ yìí fún mi? | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
K9SWG | Ìránṣẹ́-oúnjẹ náà fi ọ̀bẹ gé ara rẹ̀ lọ́wọ́ nígbà tí ó ń dáná. | yoruba | male | 18-29 | phase 1 | |
II8KP | Wọ́n máa n fi ràǹkúnmí gbé àwọn ọjà àti àwọn èso oko ní ayé àtijọ́ | yoruba | female | 18-29 | phase 2 | |
3O3RN | Àwọn olóògùn ma dúró lórí oògùn tuntun àti àwọn ìtọ́jú | yoruba | female | 30-over | phase 1 | |
2DBMP | Ìtọ̀ suga wọ́pọ̀ láàrin awọn arúgbó | yoruba | female | 30-over | phase 1 | |
R37L2 | Ṣé o ti ṣe irun kọjúsọ́ko rí? | yoruba | female | 6-17 | phase 1 | |
MZLHM | Rárá o, obìnrin kì í jẹ ọba aládé nílẹ̀ Yorùbá àyàfi adelé | yoruba | male | 18-29 | phase 2 | |
ZHR4X | Mo fẹ́ kí o gbin igi ọsàn sí ilẹ̀ tí wọ́n ti ro yẹn. | yoruba | female | 18-29 | phase 2 | |
MZLHM | Rárá, kò ní kọ́ wọn nípa òǹkà iye | yoruba | male | 18-29 | phase 2 | |
JJGZX | Bi owó ba ṣe wa nilẹ si ni ọmọ ma ṣe dagba sí. | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
UGPLR | Máì tí ì lọ ibùdó ọkọ̀ ojú omi nísinyí | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
E9LKY | Bu oúnjẹ ẹ̀gbọ́n rẹ báyìí! | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
YT0T2 | Gbogbo ilé ìtura máa ń ní ilé oúnjẹ. | yoruba | male | 18-29 | phase 2 | |
HZM4L | Èèsó kan gún táyà ọ̀kadà mi | yoruba | female | 30-over | phase 2 | |
I1W1C | Ǹjẹ́ àwọn èṣùn ti wọn fí kàn jẹ́ otitọ́? | yoruba | male | 18-29 | phase 1 | |
ZHR4X | Mo rin ìrìn-àjò lọ sí Kano pẹ̀lú ọkọ̀ ojú irin. | yoruba | female | 18-29 | phase 2 | |
C4N5S | Ìrántí máa wà nínú àwọn fíìmù náà | yoruba | female | 6-17 | phase 1 | |
OWSIZ | Ilé iṣẹ́ Tuyil ló ṣe òògùn ẹ̀jẹ̀ tí mo lò lánàá. | yoruba | male | 18-29 | phase 1 | |
MZLHM | Ọkùnrin náà sọ pé, Tẹ bírèkì náà! | yoruba | male | 18-29 | phase 2 | |
LBMHF | Bí a ba yàrá, a leè tẹ ìwé ogurun ní ọ̀la | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
5D52S | Gèésà kún fún ẹja táyítọ́sì | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
Q7FW1 | Ẹlẹ́ṣọ̀ọ́ ilé túbú ni mí. | yoruba | female | 18-29 | phase 2 | |
8CGWQ | Ṣé ìṣó wà ní ọwọ́ rẹ | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
E69XO | Báwo ni a ṣe ń kìí àwọn àgbẹ̀ ni ilẹ̀ Yorùbá? | yoruba | male | 18-29 | phase 1 | |
8C1U5 | Sọ́ọ̀bù àgbẹ̀dẹ̀ wà ní ẹgbẹ́ ààfin Ọba | yoruba | male | 30-over | phase 1 | |
N4JQD | Bose lò si ilé itúrá yèn làná | yoruba | female | 30-over | phase 1 | |
II8KP | Ẹ máa polówó ọjà yín lórí ìkànnì ìbánidọ́ọ̀rẹ́ gbogbo! | yoruba | female | 18-29 | phase 2 | |
71VHS | Àwọn ẹ̀sìn àjèjì kàn dé bá yẹn, wón jẹ̀ bẹ̀rẹ̀ sí ní pe awon ẹ̀sìn ìbílẹ̀ wa ni ẹ̀sìn Kèfèrí. | yoruba | female | 6-17 | phase 1 | |
77Y1D | Mo kọ bí wọn ṣe n yan adiẹ nílé ẹ̀kọ́ oúnjẹ. | yoruba | female | 6-17 | phase 1 | |
7TZW9 | Èdè Lárúbáwá ni èdè Jọ́dánì. | yoruba | male | 18-29 | phase 2 | |
ZLOOP | Àwọn aṣojú ló ń ṣojú ẹgbẹ́ òṣèlú tí wọ́n ní ìfẹ́ sí | yoruba | male | 18-29 | phase 2 | |
NOSZI | Osù méjìlá ló wà ní ọdún kan | yoruba | female | 30-over | phase 1 | |
MXTT9 | ẹ̀gẹ́ tí a yan ló ń di garri tí a fí ń ṣe ẹ̀bà | yoruba | male | 30-over | phase 2 | |
33QY9 | A máà ń fi bọ́kẹ̀ẹ̀tì gbé omi. | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
AVOG6 | Bẹ́ẹ̀ni, mà á ra ìwé-ìròyìn. | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
RREC0 | Awọn anfani ti awọn ipanu ọjọ iwaju le pẹlu ilọsiwaju awọn aṣayan mimọ ilera pẹlu suga idinku ati awọn eroja alara lile | yoruba | male | 6-17 | phase 1 | |
4FR3A | Òrùlé Gerrald ni a lò fún ilé yìí | yoruba | female | 30-over | phase 1 | |
TQKTS | Jáde kúrò nínú ọọlú kí o sí tí ilẹkùn ní kánkán! | yoruba | male | 30-over | phase 1 | |
1WS51 | Adé and Folú yóò gbá bọ́ọ́lù lọ́la. | yoruba | female | 30-over | phase 1 | |
XL6JK | Má ṣè tí tú àwọn ìwọ̀yè ìṣúnmọ̀ púpọ̀ fún ìwé ìtàn jẹ́ ọhun tí olúdárí sọ̀ fún mi lána. | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
43FB0 | béèni o ṣe aìgbọràn sí Bíbélì. | yoruba | female | 30-over | phase 2 | |
HNSNF | èwòn òrun méjì ní gbajumọ yén yóò wọ. | yoruba | female | 18-29 | phase 2 | |
CSMDP | Rárá o, ọmọ mi ò mọ wọ́ọ̀tì ta. | yoruba | female | 18-29 | phase 2 | |
C2K10 | A da ọmọ-ogun mọ ni ode oni. | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
IG3S1 | Èrọ ìgbaféfé orí àjà náà ti bàjé | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
UYLLZ | Biola ma ń jẹ́ písà | yoruba | male | 18-29 | phase 1 | |
1K887 | Gbogbo nudulu ti a jinna ninu ile ni a pese sile nipasẹ mi. | yoruba | male | 18-29 | phase 1 | |
KY5I7 | Inú ihò ni ọ̀kẹ́ré má ń gbé. | yoruba | female | 30-over | phase 2 | |
FTZ03 | Olùkọ́ rè ni ó tọ́jú rè | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
MZLHM | Ilé ìgbé wa ni ó tóbi jù nínú gbogbo yunifásítì wa. | yoruba | male | 18-29 | phase 2 | |
43FB0 | Ṣé o ma wá sí àjọ̀dún orin Àṣàkẹ́? | yoruba | female | 30-over | phase 2 | |
DMM7Q | Mo fẹ́ ìmò nípa báńkì aláìní èlé. | yoruba | male | 30-over | phase 1 | |
OVFI5 | Àkàrà Òṣú jé ipanu to gbajumọ ní ilè yorùbá | yoruba | female | 18-29 | phase 2 | |
UYTD3 | Ǹjẹ́ o lọ sí ilé ẹ̀kọ́ fún ìmọ̀ ẹ̀sìn? | yoruba | male | 18-29 | phase 1 | |
W8MQ2 | Wọ́n pa ètò ìṣèjọba ìbílẹ̀ náà rẹ́ ní ọdún márùn sẹ́yìn | yoruba | female | 30-over | phase 2 | |
XL6JK | Nígbà wọ̀ ni baba rẹ̀ gẹ́ igi àpùú lúlẹ̀? | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
35WFP | Ewúro ṣeé jẹ nítorí Ó dára fún ìlera. | yoruba | female | 18-29 | phase 1 | |
ADH7T | Smoothie' jẹ́ òkan lára ohun mímu elérìndòdò eléso | yoruba | female | 6-17 | phase 1 | |
KY5I7 | Ọmọ bàbá mi ní bẹ́lìtì aláwọ̀ pálí. | yoruba | female | 30-over | phase 2 |
End of preview. Expand in Data Studio
README.md exists but content is empty.
- Downloads last month
- 46