Dataset Viewer
Auto-converted to Parquet Duplicate
audio
audioduration (s)
0.06
25.8
transcription
stringlengths
4
183
Lọ ṣíbẹ̀ ko lọ ṣèké fún mi lọ́làá nípa ohun tó ṣẹlẹ̀.
Wàá pa òwe rẹ ní ọ̀la
Àwọn Krìstẹ́nì ma ń jọ́sìn ní ṣọ́ọ̀ṣì ní gbogbo ọjọ́ ìsinmi
Ṣé o ti rí nǹkan oṣù rẹ bí?
Emi yoo ka diẹ sii nipa awọn igi moringa
Mo n fojú sónà sí níní ònà tuntun láti ma po kankéré
Ọ̀nà táwọn atukọ̀ òkun máa ń gbà bá ara wọn sọ̀rọ̀ ni pé wọ́n máa ń sọ̀rọ̀
Báwo ló ṣe máa jẹun nínú yàrá lọ́la nígbà tí àwọn ọ̀rẹ́ẹ̀ rẹ máa jẹun ní pálọ̀?
Aṣọ nọọsi yóò jẹ́ ìtura fún wọn
Báwo ni wọ́n ń ṣe lè efo lọ́jà.
Rárá, olùkọ́ ni ó bá àwọn ọmọ ilé-ìwé sọ̀rọ̀ nípa ìbọ̀wọ̀.
Ṣe o ri bọọlu ni orí pápá?
Ẹ̀sìn Ábúráhámù jẹ́ ẹ̀sìn tó wá láti ẹ̀sìn pàtó kan, ta mọ̀ sí Ẹ̀sìn Judaism, Kìtẹ́ẹ́nì àti Islam.
Ọkùnrin náà ń fẹ́ dókítà rẹ̀
Ọ̀pọ̀ dókítà ni yóò wọ súkúrọ́bù ní ilé-ìwòsàn.
Emi yoo ni ifẹ lati ṣe gige gigun ejika ṣugbọn ni ibanujẹ Emi ko ni irun gigun
Mo ti lo oògùn náà
Awọn awujọ iwaju le yipada kuro ni sisọpọ awọn ihuwasi kan pato bii ofofo pẹlu awọn obinrin nikan
Ìyá ọlá máa ń rán aṣọ ọlọ́pàá
Ọmọ ile-ikawe ṣe iranlọwọ fun awọn ọmọ ile-iwe ati awọn olukọ ni iraye si awọn orisun eto-ẹkọ
Bàbá Títí ní dandan kó ní tábìlì ègbé àga.
Bàtà jẹ́ ohun tí a ń wọ̀ sí ẹsẹ̀ láti fi dabobo ẹsẹ̀
Rárá, ó ní òun kò ní wá pẹ̀lú ìgbá náà.
Taló f'òpin sí fífi owó ẹyọ ṣe óńka?
Ìyá mi yóò ra epo pupa ni ilé-ìtajà ńlá.
Má ṣe fi ìbọn bàbá rẹ̀ seré mọ́ láíláí .
Ìdènà ipanilaya le lo awọn ọgbọn ilọsiwaju ati awọn idasi.
Rárá, Shínà Peters ọ̀ ní ṣeré ní ibi ayẹyẹ náà ní ọ̀la
íyará ikáwe jelésímí, ni erò aworán kan.
Òǹkàwé akọ́ṣẹ́mọṣẹ́ ni ẹ̀gbọ́n mi
Ọ̀la ni àwọn awakọ̀ ojú omi náà wí pé àwọn yóò pa ẹja bọ̀
Ilé ìwé ẹ̀kọ́ ní àwọn ohun èlò fún ẹ̀kọ́ kíkọ́.
Ìdí tó rọ̀ mọ́ abẹ́ dídá jẹ́ ti àṣà àti ẹ̀sìn
Kí ni ẹ fún Ejò náà jẹ?
Ààrẹ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà jẹ́ ọkùnrin
O yóò parí iṣẹ náà nípasẹ̀ lilo kọnputa náà
Lẹ́hinna, àwọn kùnkùn ń kó lọ ní àárín.
Ilé alájà akọkọ ní Nàìjíríà wa ni Badagry.
Ogbúdọ̀ lọ fún ìpolongo ọ̀la
Èrèlé jẹ́ oṣù kejì nínú oṣù tó ń bẹ nínú ọdún.
Kazeem fè ṣe ògún owó.
Olórí kíláàsì ni ó ń rí sí dídarí ìrírí ẹ̀kọ́ àwọn akẹ́kọ̀ọ́.
Ọmọ náà bẹ̀rẹ̀ sí ní rìn ní ọdún méjì.
Ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn olóṣèlú ni kò ṣe olóòótọ́.
Ẹwà ní mọ fẹ́ jẹ.
Awọn iru èrò bíí ResearchGate àti Academia ṣè iranlọwọ́ fún awọn oníwádì Naijíríà àti awọn ọjọ́gbọn láti ṣíṣẹ̀ papọ̀ àti pin imọ.
Mo jẹ kaṣú kí n tó sùn lánàá.
À ń lọ sí ilé ìjọsìn lọ́jọ́ ìsinmi
èmi àti Olùdarí agbègbè ọkọ òfurufú tí di ọrẹ
Ọ̀gẹ̀dẹ̀ tí mo kó sínú àpò tí tán.
Lọ́géèjì ní àwọn ẹrù ti àwọn a rin ìrìn àjò máa n gbé dání
Ṣé o rí ọ́fììsì akápò naa?
Mo fẹ́ máa kọ́ bí wọ́n ti ń se oúnjẹ ìgbàlódé lórí ìkànnì Youtube
Lọ́ ra ọṣẹ ìfọyín wá
Pe ọ̀gá ilé-ìwé báyìí!
Àwọn ilé-ìwòsàn ní ọjọ́ iwájú lè ṣètò àwọn ẹ̀ro ìmọ̀ síáyẹ́nsì fún ìlera pípé fún aláìsàn
Awọn ilẹ̀-ifọ̀wọpamọ míkrófáìnánsì ṣe atilẹ̀yin awọn iṣowo iwọn kẹkẹre ni Nàìjíríà.
Òróró nìkan ni a lè fi dín ẹyin
Emi yóò lo girètạ làti gé ésò kàbèeji yii.
Baba mi feran jijẹ ọbẹ Ewedu Soup pelu amala.
Ọkọ ayọkẹlẹ máa ṣiṣẹ lati ará títàn ìṣìnà.
Yóò fọ́ ìgò kejì lórí ìyàwó rẹ̀
ràrá mi'o ní jé ewé Moringa.
Rárá, mi ò san owó ẹgbẹ́.
Máa lọ ewé ólífì fún ẹ̀jẹ̀ ríru ìyá àgbà.
Bẹ́ẹ̀ ni, aṣọ́nà náà yẹ báágì rẹ̀ wò.
Ayò kò parí ẹ̀kọ́ rẹ̀ ninu èdè Gẹ̀ẹ́sì àti lítíréṣọ̀ rẹ̀.
Ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn ènìyàn ni ó ń parí ẹ̀kọ́ wọn sí ilé ẹ̀kọ́ gírámà.
Ǹjẹ́ Bísí àti àwọn ọ̀rẹ́ rẹ̀ ni àwọn ọlọ́pàá kó lánàá?
Ó fẹ́ràn láti máa ṣiṣẹ́ lórí Instagram.
Dákẹ́! Ìwọ lo gbé dòdò náà.
ọ̀ọ́dúnrún ó lé mẹ́rin jẹ́ onka púráìmù
Ní ọjó ìkokanlélógún ní oṣù agemo
Rántí ọmọ ẹni tí ìwọ n se
Àwọn ọ̀dọ́mọdé wọ̀nyí ń fẹ́ra wọn lórí ẹ̀rọ ayélujára.
Lu sọ́jà tó rí mi fín lálùbami lọ́la.
Wọ́n wọ ọkọ̀-òfurufú lọ sí Àbújá lánàá.
Bisikíìtì kò wọ́pọ̀ nílẹ̀ Yorùbá láyé àtijọ́
Gbogbo táyà náà kún fún eruku.
Ó kígbe, 'Máa sáré lọ!
oúnjẹ àyànfẹ rẹ ni eko áti àkàrà .
Bẹ́ẹ̀ni, mo mọ ẹni tí ó ń kun jú rẹ
Àwọn ìjọba máa ń sọ̀rọ̀ lòdì sí ìwà ipá ètò ìdìbò ní gbogbo ìgbà.
ó ń máa ń lọ sí ilé àwọn àkàndá dáadáa
Bàbá yóò ra kẹrosíìnì láti se oúnjẹ
Ìyá rẹ̀ gba owó láti ilé ìfowópamọ́ láti kọ́ ilé
Símẹ́ǹtì yìí yóò lè gan-an tí òjò bá paá.
Àwọn akẹ́kọ̀ọ́ wa ti lọ fún ìdíje badminton.
Irú yen máa bàjẹ́ kí o tó di ọ̀la.
Mi ò tíì rí ibi tí ọkọ ofurufu ti fa ìlà sójú Òfurufú rí.
Bawo ni awọn oṣere fiimu ṣe aṣeyọri ilosiwaju ati ṣiṣatunṣe ni awọn iṣelọpọ imusin?
Kọ́lá máa jáwé amáraró lọ́la.
There is an express way in Ilé Ife
Ìyá mi nífẹ̀ẹ́ sí ìjọ tuntun náà.
Àwọn akẹ́kọ̀ọ́ kọṣẹ́ sínú ìwé wọn.
Ibo ni Abidjan wa?
Iya mi jẹ iya agba ni bayi
Ní àná, mo lọ sí ibùdó ìṣeré láti lọ pàdé olólùfẹ́ mi
Ojúbọ jẹ́ ibi mímọ́ tí ó wà fún òrìṣà tàbí ẹ̀mí kan pàtó.
Erin kò ní pẹ́ di ẹranko ilé ni ọdún di ẹ síí isinyi
End of preview. Expand in Data Studio
README.md exists but content is empty.
Downloads last month
39