Dataset Viewer
Auto-converted to Parquet Duplicate
transcript
stringlengths
4
4.69k
audio_id
stringlengths
28
34
speaker_id
stringclasses
413 values
gender
stringclasses
2 values
age_group
stringclasses
4 values
education
stringclasses
3 values
domain
stringclasses
4 values
type
stringclasses
1 value
split
stringclasses
1 value
language
stringclasses
1 value
audio_path
audioduration (s)
0.89
379
allah àá máa bùkún fún yín o
yor_f_YECT1F33_ev_spontaneous_038
YECT1F33
female
15-29
Tertiary
EV
spontaneous
train
yor
lọ́jọ́ ìṣẹ́gun tusidee ọjọ́ [um] kẹfà oṣù kẹfà ọdún yìí ni ọbaṣẹ́kì fi àtẹ̀jáde yìí lédè [um] fáwọn oníròyìn
yor_m_YECT2M16_ev_spontaneous_369
YECT2M16
male
30-45
Tertiary
EV
spontaneous
train
yor
daba itoju [um] ti ale lo fun asthma to n fa isoro lati [um] mi [um]
yor_m_YHTT3M3_he_spontaneous_266
YHTT3M3
male
46-60
Tertiary
HE
spontaneous
train
yor
àwọn ìwé àdéhùn ilẹ áfíríkà ń ṣe ìdàgbàsókè ní àwọn ọjà owó orí àgbáyé
yor_m_YBUT2M24_bu_spontaneous_478
YBUT2M24
male
30-45
Tertiary
BU
spontaneous
train
yor
baálé pàápàá kò fọrọ [um] ohun jàfírà tó fi lọọ sọ [um] fáwọn ọlọpàá
yor_m_YECT1M8_ev_spontaneous_018
YECT1M8
male
15-29
Tertiary
EV
spontaneous
train
yor
àwọn sójà mú géńdé mẹta pẹlú káàdì ìdìbò ẹgbẹrún kan ààbọ nínú ilé àkọkù
yor_f_YECT3F6_ev_spontaneous_081
YECT3F6
female
46-60
Tertiary
EV
spontaneous
train
yor
mo sábà fi aṣọ pẹ̀lẹbẹ sínú àpò mi kí n lè pa dà irísí tí mo bá fẹ́
yor_f_YECT2F14_ev_spontaneous_321
YECT2F14
female
30-45
Tertiary
EV
spontaneous
train
yor
iléeṣẹ ọlọpàá kìlọ fáwọn ọdọ ẹ má daṣà má gba fẹnikẹni mọ ó lè dá rògbòdìyàn sílẹ láàrin ìlú
yor_f_YECT3F5_ev_spontaneous_207
YECT3F5
female
46-60
Tertiary
EV
spontaneous
train
yor
mi o le kuro nibikan sibomiran tabi se ohunkohun sugbon mo ni imolara irora
yor_m_YHTT2M21_he_spontaneous_026
YHTT2M21
male
30-45
Tertiary
HE
spontaneous
train
yor
wọ́n ti ṣe àyẹ̀wò àrùn fún mi wọ́n sì sọ pé mi ò ní àrùn kankan
yor_f_YHTP1F1_he_spontaneous_116
YHTP1F1
female
15-29
Primary
HE
spontaneous
train
yor
kí ló lè jẹ́ èyí? kí ni mo [um] ní láti ṣe? ẹ ṣeun!
yor_f_YHTT1F1_he_spontaneous_407
YHTT1F1
female
15-29
Tertiary
HE
spontaneous
train
yor
kin ni oun fa egungun eyin orun ti ko le mi?
yor_f_YHTT2F1_he_spontaneous_288
YHTT2F1
female
30-45
Tertiary
HE
spontaneous
train
yor
mojúbà ọlọrun olófin olódùmarè ọba àkọdá aiye aṣẹdá ọrun
yor_m_YECT2M10_ev_spontaneous_471
YECT2M10
male
30-45
Tertiary
EV
spontaneous
train
yor
[um] o le nilo awọn idanwo ẹjẹ kan tabi usg abdomen lati ṣe ayẹwo si irora naa [um]
yor_m_YHTT2M5_he_spontaneous_113
YHTT2M5
male
30-45
Tertiary
HE
spontaneous
train
yor
adájọ ti ju adẹrìnínpọṣónú ilé wa nni trinitylay sẹwọn o
yor_f_YECT1F73_ev_spontaneous_166
YECT1F73
female
15-29
Tertiary
EV
spontaneous
train
yor
mai gemu [um] tí ìnagijẹ rẹ ń jẹ godara ló pè ní olórí ikọ burúkú [um] náà
yor_m_YECS1M5_ev_spontaneous_083
YECS1M5
male
15-29
Secondary
EV
spontaneous
train
yor
mo ti gbiyanju yoga yọju mimi emi [um] ko le tẹsiwaju mọ
yor_m_YHTT3M5_he_spontaneous_479
YHTT3M5
male
46-60
Tertiary
HE
spontaneous
train
yor
a jíròrò kókó tó le fa ìjà kí a má bà a padà ní ọjọ iwájú
yor_f_YECT1F22_ev_spontaneous_018
YECT1F22
female
15-29
Tertiary
EV
spontaneous
train
yor
ìyẹn ló ṣe jẹ́ pé ọláyíwọlá tí í ṣe aláàfin àná ni wọ́n fi jọba nígbà náà
yor_f_YECT1F54_ev_spontaneous_407
YECT1F54
female
15-29
Tertiary
EV
spontaneous
train
yor
báwo ni a ṣe lè tọ́jú ọgbẹ́ tó wáyé látàri ìṣubú?
yor_m_YHTT2M6_he_spontaneous_082
YHTT2M6
male
30-45
Tertiary
HE
spontaneous
train
yor
ọkàn-àyà rẹ̀ ẹ̀dọ̀fóró rẹ̀ àti ọpọlọ rẹ̀ kò ṣe nǹkan kò ṣe nǹkan kan
yor_f_YHTT1F18_he_spontaneous_165
YHTT1F18
female
30-45
Tertiary
HE
spontaneous
train
yor
ó kópa nínú àwọn ètò ìtọni láti kọni àti láti tẹsíwájú nínu kíkọ ẹkọ sí i
yor_f_YECT1F95_ev_spontaneous_181
YECT1F95
female
15-29
Tertiary
EV
spontaneous
train
yor
lẹyìn táwọn agbanipa yìnbọn pa kọmíkànnà yìí tán ni wọn gbé òkú ẹ sílẹẹgbọnsẹ ilé ẹ
yor_f_YECT3F7_ev_spontaneous_548
YECT3F7
female
46-60
Tertiary
EV
spontaneous
train
yor
yẹra fún bíbẹrẹ àti gbígbé ẹrù wíwúwo fún ọjọ mẹta
yor_m_YHTT2M5_he_spontaneous_419
YHTT2M5
male
30-45
Tertiary
HE
spontaneous
train
yor
ọlọwálé mutí yó lọjọ ìdìbò níbi tó ti ń sá fọlọpàá ló ti lari mọ kọlufèétì
yor_f_YECT1F73_ev_spontaneous_536
YECT1F73
female
15-29
Tertiary
EV
spontaneous
train
yor
ó sọ àwọn àṣìṣe rẹ̀ fún wọn kí wọ̣́n lè yẹra fún irú ìfàsẹyìn bẹ́ẹ̀
yor_f_YECT2F2_ev_spontaneous_256
YECT2F2
female
30-45
Tertiary
EV
spontaneous
train
yor
wọn ń kọja àwọn àdéhùn atijọ kí wọn lè ní ipa tuntun
yor_m_YBUT2M17_bu_spontaneous_520
YBUT2M17
male
30-45
Tertiary
BU
spontaneous
train
yor
wọ́n ní èèyàn tó tiẹ̀ ti lè kọ́kọ́ fi ẹgbẹ́ bàbá bàbá ẹ̀ ṣe ọkọ kí [um] lohun tó tún kù [um]
yor_f_YECT1F19_ev_spontaneous_341
YECT1F19
female
15-29
Tertiary
EV
spontaneous
train
yor
O nilo isọdọtun ẹnu ni kikun nitori ọpọlọpọ awọn eyin re ti bajẹ
yor_f_YHTT1F3_he_spontaneous_338
YHTT1F3
female
15-29
Tertiary
HE
spontaneous
train
yor
mo ṣàlàyé pé mo lè ṣe ìrànlọ́wọ́ ní àkókò iṣẹ́ ṣùgbọ́n kì í ṣe pẹ̀lú iṣẹ́ ti ara ẹni
yor_f_YECT1F1_ev_spontaneous_429
YECT1F1
female
15-29
Tertiary
EV
spontaneous
train
yor
Àkójọpọ́ akosile Àkáǹtì, Ìlànà eto ìṣirò.
yor_m_YBUS1M1_bu_spontaneous_004
YBUS1M1
male
15-29
Secondary
BU
spontaneous
train
yor
wọ́n pín àkókò iṣẹ́ kí wọ́n má baà lo ara wọn ju bí ó ti yẹ lo
yor_f_YECT2F2_ev_spontaneous_262
YECT2F2
female
30-45
Tertiary
EV
spontaneous
train
yor
ó ní eré burúkú tí ọ̀kan lára àwọn dẹ́rẹ́bà ọkọ méjì ọ̀hún ń sá bọ̀ lọ ṣokùnfà ìṣẹ̀lẹ̀ náà
yor_f_YECT1F108_ev_spontaneous_341
YECT1F108
female
15-29
Tertiary
EV
spontaneous
train
yor
wọn ṣàyèwò ipa tí àwọn ìgbìmọ ilé iṣẹ ní láti gbárùkù ti iṣẹ wíwá ní orílẹ èdè
yor_m_YECT1M10_ev_spontaneous_328
YECT1M10
male
15-29
Tertiary
EV
spontaneous
train
yor
sáyẹ́ǹsì fi hàn pé àwọn onísọ̀rọ̀ lórí ayélujára ní ànímọ́ àrà ọ̀tọ̀.
yor_f_YBUT2F21_bu_spontaneous_077
YBUT2F21
female
30-45
Tertiary
BU
spontaneous
train
yor
tí ìwádìí bá ti parí ni wọn máa taari wọn síwájú adájọ kí wọn lè fimú kàtà òfin
yor_f_YECT1F75_ev_spontaneous_084
YECT1F75
female
15-29
Tertiary
EV
spontaneous
train
yor
ṣé mo lè dúró fún ọjọ́ mẹ́ta fún ọjọ́ mẹ́ta sí i kí n lè rí dókítà mi?
yor_f_YHTT2F13_he_spontaneous_251
YHTT2F13
female
30-45
Tertiary
HE
spontaneous
train
yor
[um] ó tún jẹwọ pé ọdọ enìkan nílùú akute nípínlẹ ogun lòún tọjú bright tí wọn [um] ń wá lẹkọọ pamọ sí
yor_f_YECT2F18_ev_spontaneous_523
YECT2F18
female
30-45
Tertiary
EV
spontaneous
train
yor
ayé ti bàjẹ o ọgá ọlọpàá fipá bá ọmọọdún mẹtàlá sùn mọnú ọfíìsì rẹ
yor_f_YECT3F5_ev_spontaneous_180
YECT3F5
female
46-60
Tertiary
EV
spontaneous
train
yor
[um] àwọn aṣòfin buwọ lu mílíọnù lọnà ẹgbẹrin dọlà tí tinubu [um] fẹẹ yà
yor_f_YECT1F73_ev_spontaneous_074
YECT1F73
female
15-29
Tertiary
EV
spontaneous
train
yor
ọjọ́bọ̀ tọ́sídẹ̀ẹ́ ọ̀sẹ̀ yìí ni wọ́n tóó jẹ́wọ́ pé lóòótọ́ làwọn ṣèèṣì yìnbọn sí abúlé náà
yor_f_YECT1F91_ev_spontaneous_269
YECT1F91
female
15-29
Tertiary
EV
spontaneous
train
yor
èyí ṣe àfihàn èèrú nínú ìlànà gbígbá owó-orí èyí [um] kò wọ àsùnwòn owó [um] ìjọba. owó [um] ìjọba.
yor_f_YBUT2F21_bu_spontaneous_276
YBUT2F21
female
30-45
Tertiary
BU
spontaneous
train
yor
a gbọ́dọ̀ máa ṣe àyẹ̀wò láti rí i pé gbogbo ara wà ní ìlera pípé
yor_f_YHTT3F3_he_spontaneous_372
YHTT3F3
female
46-60
Tertiary
HE
spontaneous
train
yor
ìfijíṣẹ́ àìlérò mú àdínkù pákáleke bá àṣálẹ́ mi
yor_m_YECT2M1_ev_spontaneous_350
YECT2M1
male
30-45
Tertiary
EV
spontaneous
train
yor
ṣé mo lè lo oògùn microgynon àti trimethoprim fún àrùn inú omi?
yor_m_YHTT2M6_he_spontaneous_037
YHTT2M6
male
30-45
Tertiary
HE
spontaneous
train
yor
òní pọ́s ló lù ní jìbìtì ẹgbẹ̀rún lọ́nà méjìdínláàádọ́rùn-ún náírà
yor_f_YECT1F22_ev_spontaneous_257
YECT1F22
female
15-29
Tertiary
EV
spontaneous
train
yor
[um] mo ṣàkíyèsí lónìí pé àwọn kókó [um] kékeré pupa kan ti wà ní ìdajì ẹsẹ mi báyìí
yor_m_YHTT1M30_he_spontaneous_445
YHTT1M30
male
15-29
Tertiary
HE
spontaneous
train
yor
ọjọ etí furuufee ọjọ kẹẹẹdógún oṣù kẹsànán ọdún yìí ni onídàájọ o
yor_f_YECT1M16_ev_spontaneous_512
YECT1M16
female
15-29
Tertiary
EV
spontaneous
train
yor
èyí ló jẹ kí n pe ọlọpàá pé kí wọn ṣèwádìí tó dájú [um] lórí irú [?] èèyàn tí ọkùnrin [um] yìí jẹ
yor_m_YECT2M33_ev_spontaneous_169
YECT2M33
male
30-45
Tertiary
EV
spontaneous
train
yor
[um] aláròye gbọ́ pé ibùdó àwọn agùnbàniro [um] tó wà ní sàgámù gan-an ni àwọn oúnjẹ náà wà
yor_m_YECT3M3_ev_spontaneous_226
YECT3M3
male
46-60
Tertiary
EV
spontaneous
train
yor
àmọ́ dọ́kítà ní pé kò ní jẹ́ ìṣòro lọ́jọ́ iwájú
yor_f_YHTT2F5_he_spontaneous_169
YHTT2F5
female
30-45
Tertiary
HE
spontaneous
train
yor
imudarasi nipasẹ ounjẹ ati awọn afikun irin yoo mu aiṣedede dara
yor_f_YHTT3F4_he_spontaneous_453
YHTT3F4
female
46-60
Tertiary
HE
spontaneous
train
yor
oramah tun sọ pe àjọ rẹ yoo ṣawari awọn syndications awọn awin
yor_f_YBUT1F15_bu_spontaneous_017
YBUT1F15
female
15-29
Tertiary
BU
spontaneous
train
yor
ṣé mo yẹ ki n lọ sí ọdọ dokita tabi rara
yor_m_YHTT1M34_he_spontaneous_217
YHTT1M34
male
15-29
Tertiary
HE
spontaneous
train
yor
bẹẹ ni wọn ya fọtò papọ láti fi hàn pé nǹkan kan kò ṣe gómìnà ìpínlẹ èkó tẹlẹ náà
yor_f_YECT2F10_ev_spontaneous_468
YECT2F10
female
30-45
Tertiary
EV
spontaneous
train
yor
kí wọ́n jókòó kí wọ́n sì ronú ètò ààbò tí wọn yóò ṣe fún gbogbo ìlú yíkáyíká
yor_f_YECT1F36_ev_spontaneous_356
YECT1F36
female
15-29
Tertiary
EV
spontaneous
train
yor
nítorí bí ìta ṣe rí obìnrin ará amẹ́ríkà yìí dáná ìsínú ààwẹ̀ fáwọn mùsùlùmí ńlọrọrìn
yor_f_YECS1F3_ev_spontaneous_168
YECS1F3
female
15-29
Secondary
EV
spontaneous
train
yor
àwòlọwọ ni òun kò dúró ní west mọ
yor_f_YECT1F30_ev_spontaneous_134
YECT1F30
female
15-29
Tertiary
EV
spontaneous
train
yor
èyí ni ìdí témi àtàwọn gómìnà pdp kan fi dúró gbágbáágbá lẹyìn tìǹbù
yor_m_YECT2M49_ev_spontaneous_246
YECT2M49
male
30-45
Tertiary
EV
spontaneous
train
yor
ó fara balẹ̀ gbọ́ ohun tí ọ̀gá rẹ̀ sọ ó sì dúró de ọ̀rọ̀ tó máa sọ kẹ́yìn
yor_f_YECT2F14_ev_spontaneous_463
YECT2F14
female
30-45
Tertiary
EV
spontaneous
train
yor
àyà mí já gan-an ṣe ni mo rò [um] pé mo [um] ní àrùn jẹjẹrẹ kólọ́ọ̀nù
yor_f_YHTT2F20_he_spontaneous_176
YHTT2F20
female
30-45
Tertiary
HE
spontaneous
train
yor
ogechi ṣàlàyé iyàtọ [?] tó wà wà láàárín ìmọ nípa owó àti ìmọ ẹrọ
yor_f_YBUT1F19_bu_spontaneous_418
YBUT1F19
female
15-29
Tertiary
BU
spontaneous
train
yor
nítorí ẹ la ṣe rí i dájú pé kò sí ọtá kankan nínú gbogbo ìbọn tá a gbé lọ síbẹ
yor_f_YECT3F3_ev_spontaneous_016
YECT3F3
female
46-60
Tertiary
EV
spontaneous
train
yor
gbèsè tí kò tí kò dára gbèsè tí a kì í lè gba padà
yor_m_YBUT2M18_bu_spontaneous_403
YBUT2M18
male
30-45
Tertiary
BU
spontaneous
train
yor
mò ń lo advil [um] lẹẹkan lójúmọ báyìí kò dẹ ṣe nǹkankan sí [um] i
yor_m_YHTT1M34_he_spontaneous_551
YHTT1M34
male
15-29
Tertiary
HE
spontaneous
train
yor
gẹ́gẹ́ bó ṣe sọ lóòótọ́ ni wọn kọ lu ààfin
yor_f_YECT3F2_ev_spontaneous_021
YECT3F2
female
46-60
Tertiary
EV
spontaneous
train
yor
ààrẹ amẹ́ríkà joe bidden mọríbó lọ́wọ́ àìsàn jẹjẹrẹ àwọ̀ ara
yor_f_YECT1F50_ev_spontaneous_418
YECT1F50
female
15-29
Tertiary
EV
spontaneous
train
yor
lẹyìn [um] tí àwọn ajinígbé gba mílíọnù mẹrin [um] ayọ alábi tí wọn jí gbé ní kwara ti kú
yor_f_YECT3F2_ev_spontaneous_443
YECT3F2
female
46-60
Tertiary
EV
spontaneous
train
yor
báwo ni o? ẹ ṣeun fún [um] ìwé tí ẹ kọ
yor_f_YHTT3F3_he_spontaneous_278
YHTT3F3
female
46-60
Tertiary
HE
spontaneous
train
yor
ó fi ímeèlì ránṣẹ sí mi láti fihàn mí pé àwọn àtúnṣe tí a jíròrò náà tọnà
yor_f_YECT1F38_ev_spontaneous_077
YECT1F38
female
15-29
Tertiary
EV
spontaneous
train
yor
kí ló máa ń fa ìrora ní ọ̀pá ẹ̀yìn tó máa ń gba èjìká kọjá? kọjá?
yor_m_YHTT1M25_he_spontaneous_208
YHTT1M25
male
15-29
Tertiary
HE
spontaneous
train
yor
gólùgò lásìkò yìí kò sẹni tó máa ṣe fíìmù tó máa ní òun rí èrè nítorí gbogbo nǹkan ti wọ
yor_m_YECT2M24_ev_spontaneous_513
YECT2M24
male
30-45
Tertiary
EV
spontaneous
train
yor
èyí ni pé àwọn gómìnà wà lẹ́yìn fáyemí ju ẹlòmí-ín tí kì í ṣe gómìnà lọ
yor_m_YECT2M23_ev_spontaneous_493
YECT2M23
male
30-45
Tertiary
EV
spontaneous
train
yor
wón ṣàṣàrò lórí ìdàgbàsókè wọn nígbà ìpàdé tí wón ṣe ní òpin ọsẹ ìkẹkọọ náà
yor_f_YECT3F13_ev_spontaneous_145
YECT3F13
female
46-60
Tertiary
EV
spontaneous
train
yor
àjọ nscdc ẹka ti ìpínlẹ kwara fìdí ìṣẹlẹ ọhún múlẹ
yor_m_YECT2M12_ev_spontaneous_081
YECT2M12
male
30-45
Tertiary
EV
spontaneous
train
yor
wọ́n sì sọ nípa ọ̀nà kúkúrú kan tó dára gan-an fún ṣíṣe eré ìmáralé ti ìrìn àárọ̀
yor_m_YECT2M11_ev_spontaneous_485
YECT2M11
male
30-45
Tertiary
EV
spontaneous
train
yor
lẹyìn tí ó fojú kàn ètò ìfowósílẹ jibítì ó bẹrẹ kìlọ fún àwọn ọrẹ nípa àmì ìkìlọ
yor_m_YBUT2M17_bu_spontaneous_424
YBUT2M17
male
30-45
Tertiary
BU
spontaneous
train
yor
o nira lati sọ asọtẹlẹ orisun akoran yii pẹlu alaye ti a a pese
yor_m_YHTT1M6_he_spontaneous_169
YHTT1M6
male
15-29
Tertiary
HE
spontaneous
train
yor
ó ṣe àkíyèsí pé fintech yòò láti mú ìlọsókè àti èré tí fintech ní ọdún yìí
yor_m_YBUT1M21_bu_spontaneous_514
YBUT1M21
male
15-29
Tertiary
BU
spontaneous
train
yor
ó fi àyè sí fi àyè sí iṣẹ́ kékeré tó bá ṣiṣẹ́ pẹ̀lú àsìkò
yor_m_YECT1M2_ev_spontaneous_232
YECT1M2
male
15-29
Tertiary
EV
spontaneous
train
yor
Se didi wa ni arin aya pelu iko to nilo abojuto ?
yor_f_YHTT2F5_he_spontaneous_076
YHTT2F5
female
30-45
Tertiary
HE
spontaneous
train
yor
crypotocurrency jẹ ohun tó ń ṣẹlẹ láwùjọ ní áfíríkà
yor_m_YBUT1M21_bu_spontaneous_526
YBUT1M21
male
15-29
Tertiary
BU
spontaneous
train
yor
àwọn òṣìṣẹ́ máa ń sábà jíròrò ìtọ́jú àìdára àti pínpín àwọn ọgbọ́n láti pa ìlòkulò mọ́ra
yor_f_YECT2F7_ev_spontaneous_033
YECT2F7
female
30-45
Tertiary
EV
spontaneous
train
yor
olùdámọràn pàtàkì fún gómìnà lórí ọrọ ètò ẹkọ onírèbù jamiu oláwómí [?] ló sọ eléyìí di mímọ
yor_m_YECT3M5_ev_spontaneous_358
YECT3M5
male
46-60
Tertiary
EV
spontaneous
train
yor
níṣẹ́ ni mo mí kanlẹ̀ mo ní n kò ronú lọ síbi tó ronú lọ yìí rárá
yor_m_YECT2M18_ev_spontaneous_043
YECT2M18
male
30-45
Tertiary
EV
spontaneous
train
yor
ṣùgbọn níṣẹ ni ọdaràn náà sọrọ lórúkọ ara rẹ tí kò sì pe ẹlẹrìí kankan
yor_f_YECT2F9_ev_spontaneous_237
YECT2F9
female
30-45
Tertiary
EV
spontaneous
train
yor
ṣùgbọn ládọjà kò [um] pé ẹjọ ò kódà kò jọ [um] pé ó rántí ọrọ ilé náà mọ rárá
yor_f_YECT1F40_ev_spontaneous_012
YECT1F40
female
15-29
Tertiary
EV
spontaneous
train
yor
kò yẹ kó jẹ́ fásilà ohun tí ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn olólùfẹ́ rẹ̀ ń wí nìyí pé kò yẹ kó jẹ́ fásilà
yor_f_YECT2F40_ev_spontaneous_115
YECT2F40
female
30-45
Tertiary
EV
spontaneous
train
yor
lẹyìn tí wọn gba mílíọnù méjì àwọn ajínigbé tú lukman tí wọn pàyàwò ẹ toyùntọyún ní kwara sílẹ
yor_f_YECT1F25_ev_spontaneous_128
YECT1F25
female
15-29
Tertiary
EV
spontaneous
train
yor
ó ní ìpàdé ọhún yóò wáyé ní congress hall of transcarbon hilton hotel nílùú àbújá
yor_f_YECT1F86_ev_spontaneous_361
YECT1F86
female
15-29
Tertiary
EV
spontaneous
train
yor
a kò lè yára kóra wa jọ fún irú nǹkan pàtàkì báyìí láàrin oṣù kan péré tí ọba adéyẹmi wájà
yor_f_YECT3F2_ev_spontaneous_102
YECT3F2
female
46-60
Tertiary
EV
spontaneous
train
yor
lórí ètò ìfọ̀rọ̀wánilẹ́nuwò kan tilẹẹsẹ tẹlifíṣàn kan karcel tv ṣe fún un lálẹ́ ọjọ́ ajé monde ló ti sọ̀rọ̀ ọ̀hún
yor_m_YECT2M23_ev_spontaneous_152
YECT2M23
male
30-45
Tertiary
EV
spontaneous
train
yor
n kò retí ìbẹ̀wò yìí ṣùgbọ́n ìgbádùn ìsinmi ló jẹ́
yor_m_YECT2M1_ev_spontaneous_337
YECT2M1
male
30-45
Tertiary
EV
spontaneous
train
yor
àṣírí ńlá ìdí tí pásítọ bákàrẹ fi dọrẹ tinubu lójijì rèé o
yor_f_YECT2F47_ev_spontaneous_153
YECT2F47
female
30-45
Tertiary
EV
spontaneous
train
yor
gbogbo ènìyàn n jẹ ànfààní nígbà tí àwọn mọlẹbí bá bọwọ fún àkókò ara wọn àti àkókò ara ẹni
yor_m_YECT3M3_ev_spontaneous_077
YECT3M3
male
46-60
Tertiary
EV
spontaneous
train
yor
ọpọ àwọn aráàlú ló ń sọ pé òkìkí òjijì tí pọtidé ní yìí ló ń yọ ọ lẹnu
yor_m_YECT2M8_ev_spontaneous_057
YECT2M8
male
30-45
Tertiary
EV
spontaneous
train
yor
ṣùgbọ́n ọ̀rọ̀ náà kò padà já sí ìbàjẹ́ fún arákùnrin yìí oríyìn làwọn mí-ín ń gbé fún un
yor_f_YECT1F34_ev_spontaneous_288
YECT1F34
female
15-29
Tertiary
EV
spontaneous
train
yor
léyìn tó ti ń pé lọnà ibi iṣé lópò ìgbà
yor_f_YECT1F115_ev_spontaneous_022
YECT1F115
female
15-29
Tertiary
EV
spontaneous
train
yor
kò sẹni tó ní irú ẹyin ojú yìí nínú ẹbí wa àti ìdílé bàbá pẹlú ti ìyá
yor_f_YECT1F44_ev_spontaneous_020
YECT1F44
female
15-29
Tertiary
EV
spontaneous
train
yor
bí ìpadàsẹhìn náà ṣe di ìdádúró ọpọ àwọn olùdókòwò rí iyẹ ìpín okòwò wọn bó ṣe ńyí padà gidigidi
yor_f_YBUT3F8_bu_spontaneous_017
YBUT3F8
female
46-60
Tertiary
BU
spontaneous
train
yor
End of preview. Expand in Data Studio
README.md exists but content is empty.
Downloads last month
39