audio audioduration (s) 1.54 9.81 | sentence stringlengths 12 98 | speaker_id int64 295 9.7k |
|---|---|---|
Bàbá mi ní ọ̀la la máa lọ ra ọkọ̀ náà. | 3,349 | |
Nígbà tí ènìyàn tó burú báyì bá ń ronú kó jáwọ́ nínú ìwà ìbàjẹ́, mélòómélòó ìwọ. | 3,349 | |
Tiwatọ́pẹ́ fẹ́ Tiwaladé. | 7,508 | |
Ìjàkùmọ̀ kìí rìnde ọ̀sán. | 5,223 | |
Edé mẹ́fà ni Músá fi mu Gààrí. | 8,784 | |
Gbogbo aṣọ kọ́ la ń sá lóòrùn. | 8,784 | |
Ìgbákọ tí mo fẹ́ lò dà? | 7,505 | |
Ó ti jí ẹran jẹ nínú ìṣasùn. | 3,034 | |
Òde méjì ni a ní láti dé. | 610 | |
Mo ti pinu láti má bèèrè ìrànlọ́wọ́ láti ọwọ́ enìkankan. | 3,397 | |
Lọ wo ẹ̀wà tí mò ń sè nínú kíṣìnì. | 8,784 | |
Inú omi àti orílẹ̀ ni èyàn ti lè rí ọ̀ọ̀nì. | 1,208 | |
Orí ibùsùn Àdìó ni Ṣẹfíù jókòó sí. | 2,436 | |
Lára àwọn olùkọ́ tí mo ò le gbàbé ni ọ̀mọ̀wé Shèyí Kenny. | 2,484 | |
Afẹ́fẹ́ ń kọjálọ lẹ́sọ̀lẹ́sọ̀, gbogbo ohun ń lo létòlétò. | 2,484 | |
Ra àgbálùmọ́ fún mi tí o bá ń bọ̀. | 3,034 | |
A fẹ́ lọ ra omi ní ọjà Baṣọ̀run. | 6,136 | |
Ẹwọ̀n egbére ni a dá fun Aníní. | 9,697 | |
Iyá ọba náà tún wà níbẹ̀. | 7,049 | |
Adébámbọ̀ mú àfẹ́sọ́nà rẹ̀ wá s'ọ́dọ̀ ìyá àgbà. | 2,436 | |
Ọ̀dọ̀ Ṣàngó ni wọ́n ti tọrọ ọmọ náà. | 2,121 | |
Nínú ọkọ̀ táa wọ̀ lọ s'Ọ́yọ̀ ọ́, èmi Adéyọ̀ọ́lá la jọ jókòó. | 3,397 | |
Ní ọ̀nà àkókó, wọn ò lè ní ạ̀wọn onígbá ti wá. | 7,049 | |
Gẹ́rẹ́ tí wọ́n dé ọjà ni wọ́n rí wọn ní ẹ̀gbẹ́ ọ̀nà. | 295 | |
Mo ò ní tó iye owó yìí. | 7,049 | |
Ẹ wá ra bèbí fún mi. | 8,421 | |
Wọ́n ní ká dá àjọ kí owó baà le pọ̀. | 610 | |
Tóo bá dé oko àwọn Àkànmú, wàá fẹ́ràn iṣẹ́ àgbẹ̀. | 1,208 | |
Yọ ẹ̀rọ ìbánisọ̀rọ̀ kúrò nínú iná. | 7,049 | |
Àpò ìwé ẹ̀ wà nínú aṣọ mi. | 8,421 | |
Orí ń yún mi láti ìjẹta. | 3,349 | |
Tó bá di ọdún tó ń bọ̀, mo fẹ́ lọ ṣe ọdún Kérésì ní ìlú mi. | 5,223 | |
Tẹ̀là ló jẹ́ kí gbogbo ọ̀rọ̀ yí lọ́di òkòtò báyìí. | 8,421 | |
Ilẹ̀kùn méjì ni ó wà lọ́nà ọ̀run. | 9,697 | |
Àfá ń pè'run láago márùún. | 7,505 | |
Gbà jàre! Wọn wá ọmọ'bìrin kékeré kan o. | 7,508 | |
Ẹ̀gbín ni ká máa bọwọ́ f'ọ́ba. | 9,697 | |
Ilẹ̀ẹ ta lèyí? | 9,334 | |
Bí ó ṣe ń dún hùrùhẹrẹ yẹn ń dẹ́rù bà mí. | 2,484 | |
Ọlọ́kadà ló gbá ọmọ náà. | 7,049 | |
Báwo ni mo ṣe fẹ́ parí iṣẹ́ yìí na? | 3,349 | |
Ohun gbogbo tí Ọlórun dá, dáradára ni. | 3,034 | |
Inú mí dùn lóríi bí àwọn elére ìdárayá náà ṣe fakọ́yọ lórí pápá ìṣeré. | 3,397 | |
Àwọn Ọmọ náà fẹ́ kọ́ èdè Yorùbá. | 8,421 | |
Akẹ́kọ̀ọ́ ìmọ̀ èdá èdè lìgúísììkì ni mo jẹ́. | 3,034 | |
Ta ló jẹ gbogbo oúnjẹ inú abọ́ tán? | 2,484 | |
Bọ́lá máa ń ṣe ìrànrán tí kò bá tètè sùn. | 9,334 | |
Ọgbà àjàrà ni ó yí ilé náà ká. | 7,508 | |
Onímú kékeré ni Ájàó. | 2,436 | |
Egbére jẹ́ ìyá iwin kan. | 7,049 | |
Àwọn ọ̀rẹ́ Adéṣẹwà ń jowú rẹ̀ nítorí ẹni tó ń fẹ́ nísìyí ní owó púpọ̀. | 1,208 | |
Ìrèti ń bẹ, bí ẹ̀mí bá ti wà. | 3,034 | |
Òróró gbígbóná ta bà mí nígbà tí à ń dín ẹran. | 1,208 | |
Àrèó máa ń fi ìwà tútù tanijẹ. | 3,349 | |
Aṣọ ìbora náà kò nípọn. | 2,484 | |
Àwọn ẹranko wo ló máa ń jẹ ọ̀gẹ̀dẹ̀? | 7,508 | |
A lọ s'éjìgbò ní'jọ̀ọ́sí. | 7,508 | |
Èló ni wọ́n ń ta ìwé náà? | 1,208 | |
Kí ni m̀bá tún sọ fún ẹ ju gbogbo èyí ti mo ti sọ lọ? | 1,208 | |
Asọ̀rọ̀ sọ bótò ni Kòfowórọlá. | 1,208 | |
Alòbá fi ewé wé ọṣẹ náà. | 7,049 | |
Ọjọ́ ọdún ni a bí Abíọ́dún. | 2,121 | |
Kí ọmọ olówó má ro ọmọ tálákà pin. | 7,049 | |
Ẹsítétì náà rẹwà púpọ̀. | 7,505 | |
Oògùn abẹnu gọ̀ǹgọ̀ ni wọ́n ń pèé. | 6,136 | |
Wọ́n ń dáná sí ẹ̀gbẹ́ igbó. | 295 | |
Ajíbádé ní òun ò lọ sí Kàdúná. | 3,349 | |
Àlùfáà yín tuntun ti ṣiṣẹ́ ní ìjọ wa rí. | 3,349 | |
Ìgbà tí ó ti ilẹ̀ mímọ́ dé ni ó ṣe sàráà. | 3,397 | |
Ìfẹ́ wá mi wá sílé ṣùgbọ́n mo ti lọ ìrìn àjò nígbà náà. | 2,484 | |
Kìí ṣe dúndùn inú ẹnikẹ́ni kí ọmọ rẹ́ kú. | 8,784 | |
Aya rere l'ọ́dẹ̀dẹ̀ ọkọ ni Ṣọlá. | 9,697 | |
Gbogbo ara ni mo fi kí ẹ jàre, àbúrò mi. | 2,484 | |
Ní ọjà Èjìgbòmẹkùn ni a ti ra àwọn èso ọ̀hún. | 3,349 | |
Da ṣúgà náà padà sí ibi tóo ti gbée. | 7,505 | |
Fájídé ò ní ọpọlọ bó tilẹ̀ wù kó kéré mọ. | 295 | |
Olúwa ọba o ṣé o, mo rí isó só bẹ́ẹ̀ ni mo rí ìtọ̀ tọ̀. | 3,397 | |
Èèyàn mélo lo fẹ́ rí? | 2,121 | |
Àwọn ajá igbó wà nínú igbó kìjikìji náà. | 295 | |
Ṣé o fẹ́ràn aṣọ tí ẹ̀gbọ́n rẹ fi ránṣẹ́ láti òkè òkun? | 7,505 | |
Etí rẹ̀ pẹ̀lú a sì máa gbọ́ ìgbọ́kùgbọ̀ọ́. | 610 | |
Ká má baà jìyà la ṣe bí Májìyàgbé. | 3,397 | |
Ìṣèkúṣè ni àwọn olópàá náà ń ṣe fún wa. | 3,034 | |
Ṣé o lè rìn kíá ju báyi lọ? | 295 | |
Ṣé ó ń dùn mọ́ ẹ? | 3,034 | |
Ìrìn àjò ẹgbẹ̀rún ọdún, ẹsẹ̀ kan la kọ́ máa gbé. | 6,136 | |
Kìí ṣe awọn ọmọlóòkú nìkan ni o ti ṣe ní àǹfàní tipẹ́tipẹ́. | 5,223 | |
Sáyídì ń ta Láfún ní agbègbè Ìta Àdó. | 2,436 | |
Ta ló ń lọ fún ìdíje náà? | 9,334 | |
Gbogbo wọn ni wọ́n ń forí balẹ̀ f'Ólúwa lati àárọ̀ di alẹ́. | 3,034 | |
Ohun tí a ó fẹnu jóná lé lórí iṣẹ́ yìí ni èdè àwùjọ àwọn agbèrò àti awakọ̀. | 4,310 | |
Bọ̀dá Ràṣídì ni wọ́n fún Òkìkí ní owó oúnjẹ àárò yìí. | 2,484 | |
Ẹ̀kọ́ tí mo kọ́ láti ilé ló mú kí ayé mi ṣì gbádùn báyìí. | 7,049 | |
Ẹ̀mí á ṣe púpọ̀ ọdún láyé. | 610 | |
Akíntóyè ni àbígbẹ̀yìn màmá rẹ. | 2,121 | |
Ṣoo lè jáde kúrò nínu yàrá mi. | 3,349 | |
Ti ilẹ̀kùn kí o bá mi ní ojú ọ̀nà. | 610 | |
Ọba gan ò rí ohun kankan ṣe sọ́rọ̀ ilẹ̀ yí. | 295 | |
Àwámárììdí ni ọlọ́run. | 3,397 | |
A ṣe àkíyèsí pé wàhálà yí ò ṣẹ̀ṣẹ̀ bẹ̀rẹ̀ | 2,484 |
End of preview. Expand in Data Studio
README.md exists but content is empty.
- Downloads last month
- 14