Dataset Viewer
Auto-converted to Parquet Duplicate
English
stringlengths
3
474
Target Language
stringlengths
6
516
They have storage facilities where they protect their produce until they are sold.
Wọ́n ní ibi ìkó ẹrù sí tí wọ́n máa ń kó àwọn erè oko wọn sí títí ti wọ́n yóò fi tà á.
A. The important of agriculture to the farmer.
A. Pàtàkì Iṣẹ́ Àgbẹ̀ sí àgbẹ̀.
Depressed part of the land is easily waterlogged.
Àwọn apá ibi tí ó lọ lẹ lórí ilẹ̀ náà ní omi máa ń dágún sí.
A. Routine vaccination of wild animal B. conservation of forest resources C. specification of size of tree to be felled D. grading of timbers for export
A. Gbigba abe àjẹsára fún ẹranko tí ó lágbára B. Pípa ohun ìní igbó ọba mọ́ C. Mímọ irufẹ igi tí a fi gé lulẹ̀ D. Ṣíṣe igi gẹdú dáradára láti kó lọ sí ilẹ̀ òkèèrè
-It involves the use of complicated and expensive equipment.
-Ó ní nǹkan ṣe pẹ̀lú lílo àwọn ohun-èlò tí wọ́n rújú tí wọ́n sì níye lórí
Banks may not provide loans and produce may not sell at the right price to make more money to reinvest in the business.
Àwọn ilé ìfowópamọ́ lè lá pèsè ẹ̀yáwó, àwọn erè oko sì lè má tà ní iye tí ó yẹ láti pa owó síi láti tún oko òwò náà dá sílẹ̀.
4. They are ease to handle compared to organic manures.
4. Wọ́n ṣe é lò nírọ̀rùn bí a bá ṣe àfiwé wọn sí ti èròjà abẹ̀mí ọlọ́ràá.
As raw materials (e.g. limestone, dolomite, marble) for our industries Sources of minerals (food) rock salt such as sodium chloride (table salt).
Gẹ́gẹ́ bíi àwọn ohun-elò (b.a. okùta ẹlẹfún, dolomite, marble) fún orísun ìwakùsà áwọn ilé-iṣẹ́ (oúnjẹ) iyọ àpata bíi sodium chloride (iyọ̀ tí à ń lò ní ilé).
c. Explain two disadvantages of branding 2mks
c. Ṣàlàyé àlébù ìṣààmìsí méjì. Máàkì 2
CEREAL CROPS:These crops belong to the grass family called Gramineae.
IRÚGBÌN ÈSO ONÍHÓRÓ: Èyí ni àwọn ohun ọ̀gbìn tí wọ́n jẹ́ oríṣi ẹbí koríko tí wọn ń pè ní Gírámíìnì (Gramineae)
A. River Basin Development Authority B. Operation Feed the Nation C.Expanded Programme on Immunization Programme D. Green Revolution
A. Ẹ̀ka tó ń mójútó ìdàgbàsókè omi ìlo orílẹ̀-èdè (River Basin Development Authority)B. Ètò bíbọ́ ìlú (Operation Feed the Nation) C. Ètò lórí ìmúgbòòrò abẹ́rẹ́-àjẹsára (Expanded Programme on Immunization) Programme D. Green Revolution
These three programmes were introduced by the former military presidents-Lt Gen Olusegun Obasanjo (1976); Alhaji Shehu Shagari (1980)and Gen Muhammad Buhari (1984) respectfully to encourage people to farm and return to their abandoned farms.
Àwọn ètò mẹ́ta wọ̀nyí Lt Gen Olusegun Obasanjo (1976) ; Alhaji Shehu Shagari (1980) ati Gen Muhammad Buhari (1984) tí wọ́n jẹ́ ààrẹ ológun tẹ́lẹ̀ láti gba àwọn ènìyàn níyànjú láti ṣe iṣẹ́ àgbẹ̀ kí wọ́n sì padà sí oko wọn tí wọ́n ti fi sílẹ̀.
These are the factors that determine the prices of agricultural produce.
Èyí ni àwọn ohun tí ó ma ń sọ iye owó orí àwọn irè oko tí a pèsè.
Cattle, sheep, pigs, poultry and dwarf goats are reared.
Màálù, àgùntàn, ẹlẹ́dẹ̀, ẹranko abìyẹ́ àti ewúrẹ̀ aràrá ni wọ́n ma ń sìn ní níbẹ̀.
(d) Mention one state where the following animals are mostly reared (i) goats (ii)fish (iii) bull (iv)fowl
(d) Mẹ́nuba ìpínlẹ̀ kan tí wọ́n ti ń sin àwọn ẹranko wọ̀nyí ní apá Gúúsù Nàìjíríà (i) ewúrẹ́ (ii) ẹja (iii) akọmàálù (iv) adìẹ
Bush fowl(Gallus spp), Snail (Archachatinamorgunata).
Adìẹ oko (Gallus spp), Ìgbín (Archachatinamorgunata).
19. Deforestation increases the following EXCEPT (a) desert encroachment (b) leaching of plant nutrients (c) loss of organic matter (d) moisture retention (e) soil erosion
19. Gígé igi igbó máa ń mú kí àwọn wọ̀nyí peléke síi ÀYÀFI (a)mímú aṣálẹ̀ pọ̀ sí (b) fífọ èròjà asaralóore kúrò lára ohun ọ̀gbìn (c) pípàdánù àwọn èròjà tí a kò ṣẹ̀dá (d)fífa omi mu (e) Àgbàrá
1. (a) Define Agriculture (b) State ten importance of agriculture
1. (a) sọ oríkì iṣẹ́ àgbẹ̀ (b) sọ pàtàkì iṣẹ́ àgbè mẹ́wàá
102. A marketing activity which involves the grouping of produce into various weight and sizes is known as …… A. advertisement B. grading C. packaging D. storage
102. Iṣẹ́ káràkátà tí ó da lórí pípín àwọn irè oko sí oríṣiríṣi ìwọn àti bí wọ́n ṣe tóbi sí ni a mọ̀ sí ...... A. Ìpolówó B. ìṣe ìgbéléwọ̀n C. Dídi nǹkan pọ̀ D. Fífipamọ́
6. Soil science : This branch of agriculture deals with the study of soil structure, formation, texture and nutrients.
6. Ìmọ̀ sáyẹ́nsì ajẹmọ́ erùpẹ̀ ilẹ̀ - Ẹ̀ka iṣẹ́ àgbẹ̀ yìí dále ẹ̀kọ́ nípa bí erùpẹ̀ ilẹ̀ ṣe rí, ààtò rẹ̀, bí o ṣe rí lọ́wọ́ àti àwọn èrònjà tó kó sínú.
Cold stores provide large, volume, long –term storage for strategic food stocks in case of national emergency in many countries.
Ibi ìpamọ́ tútù máa ń ṣẹ̀ tò ibi ìkọ́ nǹkan sí tó ọlọ́jọ́ pípẹ́ tóbi, gbòòrò fún ìpamọ́ àwọn oúnjẹ fún pàjáwìrì gbogbogbò tó lè wáyé lọ́jọ́ iwájú ní ọ̀pọ̀ orílẹ̀-èdè.
(2) Write out materials that are used in agro allied industries
(2) Kọ àwọn ohun-elò tí wọ́n ń lò ní áwọn Ilé-iṣẹ́ tí ó ń lo èrè oko fún iṣẹ́ wọn jáde
FARM YARD MANURE:It is a mixture of animal droppings, urine, food remains and beddings or litter.
Ọ̀RA-ILẸ̀ INÚ OKO: Èyí ni ìdàpọ̀ ìgbẹ́, ìtọ̀, àwọn àjẹkù oúnjẹ àti pàǹtí.
Farm animals have certain basic features that make them belong to a particular group .These characteristics help to differentiate them from other forms of animals and also enable some of the animals to adapt to their natural habitat .
Àwọn ẹranko oko ní àwọn àbùdá kan tí wọ́n fí wà ní ọ̀wọ́ kan pàtó. Àbùdá yìí ṣe ìrànwọ́ láti ṣe ìyàtọ̀ wọn sí oríṣi irúfẹ́ ẹranko mìíràn tí ó sì jẹ́ kí àwọn ẹranko kan fi ibùgbé wọn kọ́ra.
Subject : AGRICULTURAL SCIENCE Term : FIRST TERM Class : JSS 3 / BASIC 9
Àkórí iṣẹ́: SÁYẸ̀NSÌ IṢẸ́-ÀGBẸ̀, Sáà: SÁÀ ÀKỌ́KỌ́ Kíláásì : JSS 3/ KÍLÁÁSÌ 9
Explain the following: a) Agricultural extension b) Forestry
Ṣàlàyé àwọn nǹkan wọ̀nyí: a) Ìṣeràwọ́ fún àwọn àgbẹ̀ kékèké b) Ìmọ̀-sáyẹ́nsì ajẹmọ ohun ọ̀gbìn c) ìmọ̀ sáyẹ́nsì ajẹmọ́ gbígbìn àti ìṣàmójútó igbó
Objectives
Àwọn àṣayàn.
PIG: They are most productive of all farm animals .
ẸLẸ́DẸ̀: Awọ́n ni ẹranko oko tí a lè mú ọ̀pọ̀lọpọ̀ irè jáde.
There is low incidence of pests and diseases
Ìdààmú láti ọwọ́ kòkòrò àti àrùn kò wọ́ pọ̀.
4..What are aquatic animals ?
4..Kí ni ẹranko ajẹmódò?
Pneumonia affects what part of the animal body A. Brain B. Lungs C. Intestine D. Skin
Ẹ̀yà ara ẹranko wo ni ààrùn ẹ̀dọ̀fóró ma ń ràn A. Ọpọlọ B. Ẹ̀dọ̀fóró C. Ìfun D. Awọ ara.
Some animals were kept and later gave birth to young ones, also some of the fruits that were thrown away later germinated and bore fruits,
Wọ́n tọ́jú àwọn ẹranko kan tí wọ́n padà bí àwọn ọmọ, àwọn èso tí wọ́n sọnù padà hù tí wọ́n sì yọ èso,
8 Thekind of Agriculture in which farmers produce enough to feed himselfand excess is sold is called ____
8. Ẹ̀yà iṣẹ́ àgbẹ̀ tí àgbẹ̀ ti ń pèsè ohun tí ó bá tó láti bọ́ ẹnu ara rẹ̀ tí àwọn tí ó ṣẹ́kù sì di títà ni wọ́n ń pè ní _____
ACTIVITIES AT THE CHANNELS OF DISTRIBUTION OF AGRICULTURAL PRODUCE
IÀWỌN ṢẸ́ TÍ Ó WÁYÉ NÍNÚ ÒPÓ PÍNPÍN ERÈ OKO
5. DISEASES: Disease is a situation in plants or animals in which there is a deviation of the plant or animal from normal state of health.
5. ÀRÙN : Àrùn jẹ́ ipò lára ìrúngbìn tàbí ẹranko nínú èyí tí irúngbìn tàbí ẹranko náà yà kúrò lọ́nà ìlera pípé.
It is therefore a profit-oriented venture/enterprise.
Ó jẹ́ òwò/oko-òwò tí à ń ṣe torí èrè tó pọ̀.
livestock affected = cattle
ohun ọ̀sìn tó ń ràn = Màálù
3. PERENNIAL CROPS: – These are crops which grow and complete their life cycle in more than two years e. g. banana, orange, cocoa, coconut etc.
3.IRÚGBÌN ỌLỌ́DÙN GBỌỌRỌ: Èyí ni àwọn ohun ọ̀gbìn tí wọ́n máa ń hù tí wọ́n sì tún parí ìṣẹ̀mí wọn kọjá ọdún méjì. b. a. ọ̀gẹ̀dẹ̀, ọsàn, kókò, àgbọn abbl
52. In selecting a farmland site, the following factors are put into consideration except …….
52. Tí a bá fẹ yan ilẹ̀ oko, àwọn nǹkankan wà tó wò àyàfi.........
ROLES OF GOVERNMENT AGENCIES IN AGRICULTURAL PRODUCTION.
OJÚṢE ÀWỌN ILÉ IṢẸ́ ÌJỌBA NÍNÚ IṢẸ́ ÀGBẸ̀
These are diseases caused by viruses.
Fáírọ́sì ló fa àwọn àìsàn yìí.
2. Agricultural engineering : This is concerned with the study of farm machineries and their uses.
2. Iṣẹ́ ìmọ̀ ẹ̀rọ ajẹmọ́ iṣẹ́ àgbẹ̀: Èyí dále ẹ̀kọ́ nípa àwọn irinṣẹ́ ẹ̀rọ̀ tí à ń lò fún iṣẹ́ àgbẹ̀ àti ìlò wọn.
The supervision of accounts and bookkeeping of all operations on the farm is carried out by ____ A. Farm treasurer B. bookkeeper C. Farm managers D. Farm supervisor
Amójútó àkáǹtì àti àkọsílẹ̀ gbogbo àwọn iṣẹ́ iní oko jẹ́ ohun tí ________ máa ń ṣe. A. Akápò oko B. Aṣàkọsílẹ̀ C. Àwọn olùṣàkóso oko D.Alámòójútó oko
Of all animals living in water, fish is the most plentiful of them.
Nínú gbogbo àwọn ẹranko tí wọ́n ń gbe inú omi, ẹja ló pọ̀jù nínú wọ́n.
(IX) The bones of fish can be crushed and processed into fertilizers.
(IX) A le è lọ àwọn egungun ẹja pọ̀ láti ṣe ajílẹ̀.
The replacement of seeds that fail to germinate is called _________ (a) supplying (b) thinning (c) mulching (d) weeding
ìfidípò àwọn èso irúgbìn tí wọ́n kọ̀ láti hù ni à ń pè ní _________ (a) ìgbinrúgbìn nilẹ̀ aṣa (b) títúkúrò (c) lilé ìdanyín (d) ìfakoríko tú
What are annual crops.?
Kí ni ìtumọ̀ Irúgbìn Ọlọ́dọọdún?
Subject : Agricultural Science, Term : Second Term, Class :Jss 1, Year 7
Àkóórí iṣẹ́: Ìmọ̀ sáyẹ́nsì nípa Iṣẹ́ Àgbẹ̀, Sáà: Sáà Kejì, Kíláàsì : Jss 1, Ọdún 7 (kéje).
Fish is high in demand for health today because of low cholesterol (unsaturated fat ) content.
Ẹja jẹ́ ohun tí a n bèèrè fún lílò ní òde òní fún ìlera nítorí wí pé kò ní ọ̀rá púpọ̀.
Forms of Labour available to farmers are:
Àwọn oríṣìí iṣẹ́ tó wà fún àwọn àgbẹ̀ ni:
Fish and meat kept in this way can remain in good condition for a long time.
Ẹja àti ẹran tí wọ́n bá tójú báyìí máa ń wà ní ipò tó dáa fún ìgbà pípẹ́.
Make a ten list of the example of the following: Mammal, Non-mammals
Ṣe àpẹẹrẹ ààtò mẹ́wàá àwọn nǹkan wọ̀nyí: ẹranko abímọ, ẹranko ayẹ́yin.
49. Cotton stainer is classified as ……. Insect A. biting and chewing B. piercing and chewing C. piercing and boring D. piercing and sucking
49. A pín kòkòrò ajòwó sí abẹ́ kòkòrò......... A. gígéjẹ àti jíjẹ B. lílu àti jíjẹ C. lílu D. lílu àti fífẹnu fà
Application of manures like compost, green and farm yard manures.
Ìṣàmúlò ájilẹ̀ bí i àwọn ohun tó ti bàjẹ́ adi ajílẹ̀, ajílẹ̀ irúgbìn àti ajílẹ̀ inú oko
It gradually reduces the strength and vigour of succeeding generations
Díẹ̀díẹ̀ ó ń ṣe ẹ̀díkùn agbára àti okun fún àwọn ọmọ tó ń bọ̀ lẹ́yìn.
symptoms = the udder becomes swollen, reddened and painful
Àmì = ọmú máa bẹ̀rẹ̀ sí ní wú, yóò sì pọ́n àti yóò sì máa dùn wọ́n.
Ideally, the total pore space should be 50% of the soil volume.
Bó ṣe yẹ, ààyè àárín iyẹ̀pẹ̀ gbọdọ̀ ju 50% iye iyẹ̀pẹ̀ lọ.
1. Tractor: For pulling Farm implements and machines such as plough, harrows and planters, For driving other farm machinery.
1. Tírákítọ̀: fún fífa àwọn ohun èlò oko àti ẹ̀rọ bí i ẹ̀rọ-ìtúlẹ̀, ẹ̀rọ ìyọ koríko àti ẹ̀rọ agbin-rúgbìn, Fún wíwa àwọn ohun ẹ̀rọ oko mìíràn.
2.State 3 advantages and 2 disadvantages of mixed farming system.
2. Sọ àwọn ànfààní 3 àti àwọn àlébù 2 tí ó wà nínú iṣẹ́ ọ̀gbìn àpapọ̀.
Land is limited in supply (its amount cannot be increased in a geographical area) and thus its availability for agricultural practise is largely dependent on
Ilẹ̀ ní gbèdéke ibi tí ìpèsè rẹ̀ dé ( iye owó rẹ̀ kò ṣe é fikún ní àgbègbè kan) fún ìdí èyí wíwà rẹ fún iṣẹ́ àgbẹ̀ dálé bí
(a) Government should subsidize the price of agricultural inputs
(a) Kí ìjọba ó ṣe ìdínkù lórí iye owó àgbéwọlé ajẹmọ iṣẹ́ àgbẹ̀
1 _________ is an area of land for growing crops and or raising farm animals A. School farm b. Class room C.Dining hall D. sport complex E. Bath room
1 _________ ni apá kan Ilẹ̀ fún gbígbin irúgbìn àti sísin ẹran oko A. oko ilé-ìwé B.Yàrá ìkẹ́kọ̀ọ́ C.Gbàgede ìjẹun D. Ọgbà eré ìdárayá E. ilé-ìwẹ̀
5. State five problems of agricultural development in Nigeria and suggest two possible solutions to each.
5. Sọ́ àwọn ìṣòro ìdàgbàsókè isé-àgbẹ̀ ní Nàìjíríà kí ò sí sọ ọ̀nà àbáyọ mẹ́jì sí ọ̀kọ̀ọ̀kan wọn.
Water-logging – this also reduces soil fertility and land for farming.
Àpọ̀jù ọmi ní orí ilẹ̀- èyí náà máa ń fa ìdínkù fún ọ̀rá ilẹ̀ fún iṣẹ́ àgbẹ̀.
They are operated by a man walking behind them and used mainly for light cultivation.
Ènìyàn tí ó ń rìn bọ̀ lẹ́yìn wọn ni ó máa ń tukọ̀ wọn wọ́n sì máa ń lò wọ́n fún àwọn iṣẹ́ tí kò gúnpá
A management committee is elected on a one-member one-vote basis to direct the affairs of the cooperative.
A ó yan àwọn ọmọ ìgbìmọ̀ pẹ̀lú ètò ìdìbò, èèyàn kan, ìbò kan láti máa tukọ̀ ẹgbẹ́ náà.
Labour includes all forms of productive human efforts put into or utilized in production.
Ìṣẹ́ ní akitiyan tó bí èsò tí àwọn ènìyàn ń fi sí tàbí lò nínu ìṣèpèṣè.
3 Little labour is required in preserving the food.
3. Iṣẹ́ díẹ̀ ní a nílò láti tọ́jú oúnjẹ.
6. Fibre is the raw material for ____ industries (a) drugs (b) food (c) beverages (d) textile
Fáíbà jẹ́ ògidi ohun-èèlò fún àwọn ilé-iṣẹ́ ńlá ___ (a) òògùn (b) oúnjẹ (c) ohun mímu (d) aṣọ
Hilly and sloppy surfaces support erosion and encourage soil formation.
Àwọn pèpèlé olókè ati èyí tí ó yọ̀ lọ sílẹ̀ máa ń ran àgbàrá lọ́wọ́ ó sì máa ń ní ìgbàníyànjú ìṣẹ̀dá ilẹ̀.
Which of these is not a role of science and technology in agriculture?
Èwo nínú àwọn wọ̀nyí ni kì í ṣe ojúṣe ìmọ̀ sáyẹ́nsì àti ìmọ̀ ẹ̀rọ nínú iṣẹ́ àgbẹ̀?
98. Which of the following is not a method of fertilizer application? A. row placement B. top dressing C. broadcasting D. branding
98. Èwo nínú àwọn wọ̀nyí ni kì í ṣe ìlànà ìṣàmúlò ajílẹ̀? A. gbígbin àwọn ohun ọ̀gbìn sí ẹ̀gbẹ́ ara wọn B. ìfi ajílẹ̀ sínú erùpẹ̀ ilẹ̀ C. ìfọ́ká kóró sórí ilẹ̀
This includes watering, weeding, applying fertilizers, pruning, weeding etc.
Àwọn ìgbésẹ̀ yìí ni ifi omi wọ́n, ìtú koríko, ìṣàmúlò ajílẹ̀, gígé òpó igi tó ti bàjẹ́ àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ.
i. Farm record ii Profit and loss account iii Consumption Record iv Inventory v Farm diary.
i. àkọsílẹ̀ oko ii ìṣirò èrè àti òfò iii àkọsílẹ̀ ohun tí wọ́n lò iv Nǹkan orí igbá v.àkọsílẹ̀ rántí oko
It protects the soil against erosion
Ó ma ń dáàbòbò ilẹ̀ lọ́wọ́ ọ̀gbàrá omi.
2. State 5 properties of each types of soil mentioned in (i) above
2. Sọ àwọn àwòmọ́ márùnu-ún tí ọ̀kọ̀ọ̀kan àwọn oríṣìí ilẹ̀ tí o mẹ́nubà ní (i) lókè
Rock constitutes a significant part of the earth’s crust.
Àpata dí apá ibi òke-ilẹ̀ ayé tí ó lápẹẹrẹ mú.
These duties includes supervision of the work on the farm, arrangement work roasters, directing workers on day-to-day activities,ensuring staff welfare, organizing training of man-power in the farm, etc.
Àwọn òjúṣe ni àmójútó iṣẹ́ tí ó wà lóko, ṣíṣe ààtò iṣẹ́, dídarí àwọn òṣìṣẹ́ lórí ìṣe ojoojúmọ́, ìgbéyégbádùn àwọn òṣìṣẹ́, ṣíṣètò ìdánilẹ́kọ̀ọ́ àwọn ènìyàn tí ó ṣiṣẹ́ oko náà, abbl
35. The knowledge of packaging materials is essential because each product to be packsged has its own (a) direction (b) shape (c) properties (d) size
35. Ìmọ̀ kíkó-ọjà-jọ ṣe pàtàkì nítorí pé ọjà kọ̀ọ̀kan tí a kó jẹ ní ó ní _____ tirẹ̀ (a) ọ̀nà (b) igun (c) àbùdá (d) ìwọ̀n ìtóbi
Rabbits: Cities where poultry are successfully reared.
Ehoro: Ìlú tí wọ́n bá ti lè sín ohun ọ̀sìn abìyẹ́.
Producers: These are the farmers that are responsible for the direct production of crops and livestock.
Aṣèpèsè: Àwọn wọ̀nyí ni àgbẹ̀ tó ń ṣèpèsè àwọn ohun ọ̀gbìn àti ohun ọ̀sìn fún ara wọn.
Objective Test:
Ọ̀bìjẹ́tìfù ìdánwò ránpẹ́.
It is a source of medicinal herbs, It is a source of fibre and ropes
Ó jẹ́ orísun oògùn ìbílẹ̀ fún ìwòsàn, Ó jẹ́ orísun ikàn àti àwọn okùn.
Periodic Maintenance of Farm Machinery
Iṣètọ́jú àwọn ẹ̀rọ inú oko láti ìgbà dé ìgbà
Fowl is the most popular of all and this makes the discussion on poultry to be centred on domestic fowl .Domestic fowls are grouped into two :Local fowl and Exotic fowl.
Adìẹ ni ó gbajúmọ̀ jù lọ èyí ló jẹ́ kí ọ̀rọ̀ nípa ohun ọ̀sìn abìyẹ́ fúnka mọ adìẹ. A sì lè pín adìẹ sí ọ̀wọ́ méjì àwọn ni adìẹ ìbílẹ̀ àti adìẹ aláìṣetìbílẹ̀.
Name the 5 major feed nutrients
Dárúkọ èròjà oúnjẹ márùn-ún tó ṣe gbòógì
A bank account will be opened for the society with about three signatories to the account.
Àpò owó ilé ìfowópamọ́ yóò di ṣíṣih fún àwọn ọmọ ẹgbẹ́ àwùjọ pẹ̀lú ó kéré tán àwọn olùbuwọ́lù mẹ́ta fún àpò náà.
State any 3 functions each of the stem and the root.
Dárúkọ 3 yìówù nínú iṣẹ́ èèkàn àti egbò.
Sales of commodities in a local market.
Títa erè oko nínú ọjà agbègbè
5. Presence of sulphur in the soil.
5.Ìwa-níbí imí-ọjọ́ nínú ilẹ̀
This makes it difficult for farmers to transport their products from villages to cities and forces them to sell at local markets at relatively low prices.
Èyí máa ń fa ìṣòro fún àwọn àgbẹ̀ láti kó erè-oko wọ́n láti ìgbèríko lọsí ìlú àti láti rí dájú pé wọ́n tá àwọn erè-oko yìí ní owó tí kò pọ̀.
The flowers produce the fruits and seeds
Àwọn òdòdó máa ń pèsè èso àti kóró
The following are agricultural practices in West Africa EXCEPT (a)fishery (b)poultry (c)crop cultivation (d)hunting
Àwọn wọ̀nyí ni iṣẹ́ ṣíṣe nínú iṣẹ́ àgbẹ̀ ní apá ìwọ̀ oòrùn Áfíríkà àyàfi (a) ọ̀sìn ẹja (b) ọ̀sìn ohun abìyẹ́ (c) gbín ohun ọ̀gbìn (d) iṣẹ́ ọdẹ
9. Agriculture provides all the following EXCEPT .......A. Food B. Shelter C. Poverty D. Clothing
9. Iṣẹ́ Àgbẹ̀ ń pèsè àwọn nǹkan wọ̀nyí ÀYÀFI.......A. Oúnjẹ B. Ilé-ìgbé C. Ìṣẹ́ D. Aṣọ
It helps in cloud formation
Ó ṣe ìrànwọ́ fún dídá kùrukùru sáńmọ̀.
Permeability and Water-Holding Capacity:
Ìfamimu àti agbára ìgba omi-dání:
The purpose of this is to ensure products quantity and stable price.
Èrè ìdí èyí ní láti ri dájú pé erè oko pọ̀ ó sì ní iyé owó tó kò yẹ̀.
They are the earliest domesticated and the most widely distributed animals with high concentration in Africa and India .Goat have ability to withstand harsh weather conditions.
Wọ́n jẹ́ ẹranko abánigbé tó ti kọ́kọ́ wà tí ó sì wà ní ọ̀pọ̀lọpọ̀ agbègbè
iv) Environmental degradation.
iv) Ìbàjẹ́ àwọn nǹkan aṣàwùjọ lánfààní.
The temperature is usually maintained between 37.5°C and 39.5°C Setter:
Wọ́n máa bójútó ìgbónágbooru rẹ̀ láàrin òdíwọ̀n 37.5°C sí 39.5°C:
End of preview. Expand in Data Studio
README.md exists but content is empty.
Downloads last month
54