audio
audioduration (s)
1.54
28.9
sentence
stringlengths
17
265
Ìnuwọ́ wà ní abẹ́ tábìlì.
Kí lẹ ṣe ní kílàsì lénìí?
Awon ogbontarigi olorin kakiri orileede sagbekale bhajans abi orin isin si abe ese Shyam.
Orísìírísìí ìgbésẹ̀ la máa gbé lórí ọ̀rọ̀ yìí.
Àwọn kan gbàgbọ́, pẹ̀lú john Grant, pé àti funding crunch àti sísún ní ẹ̀kọ́ ìmòye ètò orí amóhùnmáwòrán dási láti parí eré náà.
Ní aago mọ́kànlá kọjá ogún ìsẹ́jù, iléeṣẹ́ ọlọ́ọ̀pá tí ní káwọn olùsèfẹ̀hónúhàn sún sẹ́yìn, sọ pé wọ́n nílò láti sètò ìfẹ̀hónúhàn pẹ̀lú súnkẹrẹ fàkẹrẹ tó ń kó jọ.
Ni aago kàn kojá ìséjú márùndínlógún gégé bi ẹlẹri, ọkò akérò náà lọ níbi iná aláwọ ewé, nígbàtí ọkọ̀ ayọ́kélẹ´ náà yíwọ́ níwájú rẹ̀.
Bẹ́ẹ̀ni! Ọba Tutankhamun, ti wọ́n fi ìgbà kan pè ní “King Tut” tàbí “ọba àwọn ọkùnrin”, jẹ́ ọ̀kan lára ọba Egypt àtijọ́ tí ó gbajúmọ̀ ní ayé òdi òní.
Ní àríwá, Sahel ni ó yí ẹkùn náà ká, omi òkun ní ó yí gúúsù àti ìwọ̀ oòrùn ká.
Ọwọ́ tẹ Tájù fọga tó fipá bá ọ̀dọ́mọbìnrin lòpọ̀ ní Ìpájà.
Àkókò tún jẹ́ bi a se ń ṣe àfiwẹ́ iye àkókò (gígùn) àwọn ìsẹ̀lẹ̀.
Ilé ìwé Alébíoṣù ti sọ fún àwọn akẹ́kọ̀ọ́ ẹ̀ láti padà síṣẹ́.
Ní ibi ìdíje ni wọ́n ti pàdé ara wọn.
Ìgbà márùn-ùn ọtọ́ọ̀tọ̀ ni mínísítà ètò ọrọ̀ ajé dídé láti jó
A kò mọ̀ ní àkókò yí àwọn àyípadà tí wọ́n ma ṣe àti nkan tó jẹ́kí wọ́n rí ọmọ okùnrin náà gbámú, ṣùgbọ́n ètò ilé ẹjọ́ fún ọ̀dọ́ ti bẹ̀rẹ̀.
Ẹ wo èsì tó fún iléeṣẹ́ ọmọogun Nàìjíríà lórí ẹ̀sùn kòbákùngbé.
Jọ̀wọ́ fi tọ̀wọ̀tọ̀wọ̀ ṣe pẹlú ilẹ̀ náà, pẹ̀lẹ́pẹ̀lẹ́, sùúrù àti ọ̀wọ̀. Ẹ má ṣe fi Holocaust tàbí Nazis ṣe yẹ̀yẹ.
Wọn kó àwọn ọkùnrin mẹ́fà lọ ẹ̀wọ̀n ní òkè-òkun.
Àwọn ara Ìrano lo kọ́kọ́ bẹ̀rẹ̀ si ni sin ewure ní bíi ọdún 15,0000 sẹ́yìn ní Oke Sagrosi.
Ìwé ìròyìn márùn-ún n wọ́n kọ̀ọ́ sí.
Ààyò mi àti ọkùnrin tó rẹwà jùlọ ní wọn fí ń ki ọba Adéyẹmí.
Bí ó ti máa ń ṣòro fún àwọn ẹ̀yà ara tí ó wà fún èémi ní ibi tí ó tutù, ìṣòrò ìfun wọ́pọ̀ ní agbègbè tí ó bá gbónà, àti pé ní ọ̀pọ̀ ìgbà, a máa bíni nínú gidi, ṣùgbọ́n kò léwu púpọ̀.
Àwọn jàndùkú jí agbábọ́ọ̀lù Nàìjíríà méjì gbé lópòpónà.
Hangooli ni alifabeeti kan soso ti a moomo seda ti a si n lo lojumo. Won seda alifabeeti naa ni 1444 nigbati Oba Sejongi wa lori oye (1418 - 1450.
[snap] Ọ̀gágun Abéégúnrín àti àwọn ọmọ ogun àpapọ̀ ti lọ sí ojú ogun.
Yúróòpù jẹ àkójọpò àwọn orilé-ẹ̀dẹ tó kèrè jọjọ sùgbọn pèlú ọ̀pọ̀lọpọ̀ orilé-ẹ̀dẹ olómìnira. Níwọn bí o ti yẹ kó rí, rírin ìrìn-àjò kàkàkiri ọ̀pọ̀lọpọ àwọn orilé-ẹ̀dẹ yìí túnmọ̀ sí gbígba ohun èlò ìwé ìwọ̀lú àti ìsàkóso ìwé ìrìnnà ní ọ̀pọ̀lọpọ ìgbá.
Ọlọ́pàá náà ti fi ojú ba ilé ẹjọ́ báyìí.
A o ni ti moto pale lai lai, ko orisun omi si eyinkule wa, rin lo Peru lati lo wo erunrun atijo, abi tun ile aladugbo wa ko.
Àwọn aṣòfín ní ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ ti yọ Abẹnugan Ilé bí jìgá.
[snap] Ó rò pé màá fi orí lé ọ̀nà ìlà-oòrùn padà lọsí ilé lọ sùn fún ọjọ́ díẹ̀.
Àpáta àti eruku ni wọ́n fi se pẹpẹ òṣùpá. Ìpele ìta òṣùpá ni wọ́n ń pè ní èèpa.
Ó ti yẹ kí Massa jáde fún ókéré tán títí di òpin sáà 2009.
Ìkùnà ọ̀rọ̀ kejì, tí ó gbèrò láti fòpin sí same sex civil unions, lè ṣí ìlẹ́kùn fún civil union ní ọjọ ìwájú.
Wíwá náà tún fúni lóyẹ sí ìtànkálè ti àwọn ìyé nínú ẹyẹ.
Àwọn àfihàn àwọn ilé tó mún kí ojú òpó Hong Kong rẹwà ni ati fi wé àtẹ tí ó ń dán èyí tó tàn nípa omi Victoria Harbour tó wà nílẹ̀.
Rẹ̀mi ní àfojúsùn òun ni láti ní abúlé mẹkáníkì láìpẹ́.
[breath] Àdúgbò náà máa ń dákẹ́ rọ́rọ́.
[snap] Mo ti fi àtẹ̀jíṣẹ́ ránṣẹ́ sí alága lórí ọ̀rọ̀ owó orí tí a fẹ́ san.
Túndé ló fa aṣọ ya mọ́ káńsẹ́lọ̀ obìnrin kan lára
Wọ́n sọ pé ikú burúkú ló pa Akíntọ́lá nÍbàdàn
Sugbon, awako sese sori gidi.
Ilé títúnṣe àti ọmọ títọ́ ni iṣẹ́ ti àwọn ìyá nígbà yẹn.
Ọba Olúfọlárìn Ògúnsànyà sọ fún àwọn ará Ẹ̀pẹ́ kí wọ́n dáwó
Wọ́n sàfimọ́ àwọn ará ilẹ̀ Netherlands pẹ̀lú Anna Jochemsen tó parí pẹ̀lú ipò kẹsàn án nínú àwọn obìnrin tó ń dúró ní kílàsì super-G lánàá àti Katja Saarinen ti ìlú Finland tó parí pẹ̀lú ipò kẹwàá nínú ètò kanáà.
Máṣe bá ojú òpó náà jẹ́ nípa ṣíṣà mí si tàbí àwòrán tó wà ní ogiri.
Adé ń tọrọ lọ́wọ́ ọlọ́run fún ẹ̀bùn àdúrà
Nígbà tóyá, ọ̀kan lára àwọn èrò ju orí olórí ẹ̀ṣọ́ tí wọ́n sekúpa ni Versaille síwájú ayaba tẹ́rù ti ń bà.
Máàpù ìwáádìí ẹ̀kọ nípa ilẹ̀ ohun ìwárìrì-ilẹ̀ ti orìlé-èdè, Amerika sàfihàn pẹ́ ́àwọǹ ìwárìrì-ilẹ kò sẹlẹ̀ ni Iceland ni ọ̀sẹ̀ tó sáájú.
Àwọn ọ̀tá ìtẹ̀síwájú ń sa ipá láti ba ikọ̀ Amotekun lórúkọ jẹ́
Kò s’ẹ́ni tó mọ Ifá tán.
Ta ló wọ bàtà mi.
Mi ò kí n fi bẹ́ẹ̀ ṣeré níta.
Ó fi ipá báa lò pọ̀ lánàá.
Ohun rere ni yóò ma jẹ ti wa.
Nígbà tí ènìyàn tó burú báyìí bá ń ronú kó jáwọ́ nínú ìwà ìbàjẹ́, mélòómélòó ìwọ.
Ilé ìwé girama kan ní ìpínlẹ̀ Ogun ti jónà nítorí àìní omi.
[breath] Wọ́n gbin òdòdó sí àárín ọgbà ilé náà.
Ẹ̀yí mú ọpọlọ wá, torí wípé kò dà bí ẹni wípé pé ayé ń yí, àbí ó dàábẹ̀?
Ètò ọ̀gbìn aládàáni jẹ́ ètò ọ́gbìn tí a má ń se láti pèsè oúnjẹ tí yíò fún àìní àgbẹ̀ àti àwọn ará ilé rẹ̀.
Ta ni àwọn tó fi ẹnu kò lẹ́nu nínú ètò tí a wò lánàá?
Láti orílèèdè China ni èrò àtinúdá náà ti wá, níbi tí èso igi púlùmù ti jẹ́ òdòdó tí ó yááyì jùlọ.
[snap] Ìlú Ìlọrin ní àwon olorin dadakùádà wọ́pọ̀ sí.
Wọ́n ti yọ ṣẹ́kẹ́-ṣẹkẹ̀ lọ́wọ́ Ìgbòho.
Onífádé Adélabú ń ṣè ìdárò ikú ọkọ tó pa ọ̀rẹ́ rẹ̀
Olùdarí ilé iṣẹ́ amóhùnmáwòrán Ìlọrin ti kọ̀wé fi ipò ẹ̀ sílẹ̀.
Awon alawofunfun ni orile ede Turkey (iwo oorun Thrace tabi Rumelia ni ekun Balkan peninsula) kun 3% awon eeyan orile ede naa.
Ayọ̀ Ajéwọlé sọ pé òun ti bọ́ sínú ọkọ̀ tó ń lọ sí Ìlọrin
Eléyìí ni à ń pè ní pH apòògùn. O lè se asàmì pẹ̀lú lílo ohun ẹlẹ́rìndòdò pupa ti kábèjì.
Ẹ̀san ń bẹ fún ẹni tó bá ṣẹ̀ ìka.
Ọ̀rọ̀ àwọn ọmọ náà kò tiẹ̀ fẹ́ yé wa mọ́ rárá ni.
Ẹ̀bà gígan ni Bísí jẹ sùn lánàá.
Àwọn ọlọ́pàá tó wà ní ilé ìwòsàn ti wà níbẹ̀ fún oṣù mẹ́sàán
Bọ́sẹ̀ bú sí ẹkun ayọ̀ lẹ́yin tí ó parí ìwádìí.
Ní ilẹ̀ Yorùbá, bàbá ni olórí ilé.
Síwáájú si lẹ́yìn ìsọ̀tẹ̀ náà àyè láti sisé si´ sílè fún gbogbo àwọn òlùbèwò okùnrin èyí tó fi àyè gba àwọn to ní ìtalára àti pẹgẹdẹ́ jùlọ láti sẹ àsèyor.
Àwọn ọmọ ogun orí omi wà níbẹ̀.
Adéforítì ní ìforítì. [snap]
Ìgbòho ní òun ti ṣé iṣẹ́ mọkálìkì rí.
Ọ̀rẹ́ pàtàkì ni èmi àti ẹ̀gbọ́n bàbá e nígbà tó wà láyé.
Oríṣi àrùn méjọ ló máa ń ṣáábà mú aláboyún.
O fi orúkọ rẹ sílẹ̀ sínú ìwé 1998.
[snap] Ìyẹn ni pé àwọn ìlú kékèké nínú igbó yìí náà máa ń lo iná ìjọba.
Wọ́n lu ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù kan ní ọ̀mì ayò mẹ́ta sí óòdo.
Tutù ní èjí ní eyín rẹ̀.
Ìlú ìgbàani tí ò wà ní Òke Juda ni ìtàn tó múnilọ́kàn tí ó sì ti ń gbòòrò láti bí ẹgbẹ̀rún ọdúnsẹ́yìn.
[snap] Bíọ́dún kìí ṣọ́ owó náà rárá, ó lè ná gbogbo owó oṣù rẹ̀ tán ní ọjọ́ kan.
Irú àṣìtẹ̀ burúkú wo ni èyí?
Peter Costello, alákòso ìsúra orílè-èdè Australia tí o si jẹ ẹni tó sẹẹsẹẹ láti gbàjọba lówó adarí ìgbìmò ìjọba John Howard gẹ́gẹ́ bi adarí ẹgbẹ´ oẹlómìnira tí àtíléyìn hán sí ilẹ́ isẹ́ àdó olóró ní Australia.
Òtútù ń mú ọmọ tí ń sọ ìkan fún mi yí, níṣe ló ká jọ bí i adìẹ tí òjo pa.
Irú ìbéèrè wo lèyí?
Àawọ̀ wà láàrin àwọn àgbẹ̀ àti darandaran.
Ìjì líle ti gbì tó okòódínníẹ̀dẹ́gbẹ̀ta kìlómítà láàrin wákàtí (133 m/s; 300 mph).
Oúnjẹ tó dára ni ọ̀rẹ́ àwọ̀.
Àwọn èyàn ti mọ̀ nípa àwọn kemika pepe bí wúrà, fàdákà àti kọ́pa àtijọ́, torípé a lè rí wọn ní ìṣẹ̀dá ní ipò àdáyéba wọn, kò dẹ̀ le jù láti wú wọn jáda láti inú ilẹ̀ pẹ̀lú irinṣẹ́ àtilẹ̀bá.
Àwọn dókítà ti ń ṣe ìdánilẹ́kọ̀ọ́ ìmọ̀tótó fún àwọn ọ̀dọ́.
[snap] Iṣẹ́ àmúrelé tí olùkọ́ àgbà fún wa yìí le gan o.
Àyípadà ìsanwó wà fún níní ju ẹni méjì lọ nínu ọkọ́, nítorínà èyí lè wọ́n jú bí ó ti yẹ lọ.
Àwọn ọmọ ìta kọlu onírọ̀yìn kan ní ìlú Èkìtì.
Àwọn ayalégbé ní Ọgbà Lockwood gbàgbọ wípé àwọn ìdílé ogójì míràn ma dojuko lilejade, níwọ̀n tí wọn gbọ wípé àwọn Ọlọpa OHA naa ń sẹ iwádìí àwọn ohùn ìní ilé gbogbo míràn tí o seese kí wọn ni irírí ètẹ ìtànje ilé.
Ní àsìkò àmì ẹ̀yẹ̀ náà, ilé-ẹkọ́ Atlanta ti rí ìlọsíwájú lórí èsì ìdánwò.
README.md exists but content is empty. Use the Edit dataset card button to edit it.
Downloads last month
0
Edit dataset card