cleaned_text
stringlengths 6
2.09k
| source
stringclasses 2
values | language
stringclasses 1
value |
---|---|---|
Lóde òní, epo pupa ni ohun ìsebẹ̀ tí gbogbo àgbáyé ń jẹ jù lọ. | bbc | yo |
Ìròyìn inú fídíò yìí ṣe àyẹ̀wò bí wọ́n ti ṣe máa ń se epo, ibi tí ó ti ń wá àti bí ó ṣe ń gbéra sọ di ohun ṣíṣàduẹgbẹẹgbẹ̀rún inú ọbẹ̀. | bbc | yo |
Orísun àwòrán, Getty Images ara ẹ̀ṣọ́ ẹ̀yìn tí wọ́n kó lórí igi ọ̀pẹ ni wọ́n ti máa ń rí epo pupa. | bbc | yo |
Ẹkùn ìwọ̀ oòrùn Afirika ni igi ọ̀pẹ wulẹ̀ ti gbilẹ̀, àmọ̀sá lóde òní ó ti kààkàìrì àwọn ilẹ̀ olóoru lágbáyé láti leè kojú bí àwọn èèyàn ṣe ń fẹ́ ẹ sí. | bbc | yo |
Ìdí ẹ̀yin tí wọn bá kọ́ lórí igi ọ̀pẹ wọ̀nyìí ni wọn yóò kó lọ sí ibi tí wọ́n yóò ti ṣe é, tàbí lọ sí iléeṣẹ́ tí wọ́n ti ń ṣe epo pupa. | bbc | yo |
Níbẹ̀ ni wọ́n yóo ti yọ àwọn ẹ̀yìn wọnyii kúrò lára ìdí ẹ̀yin tí wọn kò bọ́ láti ọkọ̀.. | bbc | yo |
Níbẹ̀ ni wọn yóo ti yọ àwọn ẹ̀yìn wọnyii kúrò lára ìdí ẹ̀yìn tí wọn kò bọ́ láti ọkọ̀. | bbc | yo |
Ní kété tí wọ́n bá yọ ẹ̀yin yìí tán ni wọn yóò dáa sí inú ìkòkò tí wọn yóò fi ṣe é tí wọn yóò sì dáná síi lábẹ.. | bbc | yo |
Ní kété tí wọ́n bá yọ ẹ̀yin yìí tán ni wọn yóo dáa sí inú ìkòkò tí wọn yóo fi ṣe é tí wọn yóo sì dáná síi lábẹ́. | bbc | yo |
Lẹ́yìn tí wọ́n bá ṣe é tán ni wọn yóo kó o sinu èrò tí yóo lò ó tabi kí wọ́n fi ẹsẹ̀ tẹ̀ẹ́ gẹ́gẹ́ bí wọ́n ti ń ṣe ní ayé àtijọ́ láti yọ epo ara rẹ̀.. | bbc | yo |
Ara èso ẹ̀yin tí wọ́n kó lórí igi ọ̀pẹ ni wọ́n ti máa ń rí epo pupa. | bbc | yo |
Ẹkùn ìwọ̀ oòrùn Afirika ni igi ọ̀pẹ wulẹ̀ ti gbilẹ̀, àmọ̀sá lóde òní ó ti kààkàìrì àwọn ilẹ̀ olóoru lágbáyé láti lée kojú bí àwọn èèyàn ṣe ń fẹ́ ẹ sí. | bbc | yo |
Lẹ́yìn tí wọ́n bá sè é tán ni wọn yóo kó o sinu èrò tí yóo lò ó tabi kí wọ́n fi ẹsẹ̀ tẹ̀ẹ́ gẹ́gẹ́ bí wọ́n ti ń ṣe ní ayé àtijọ́ láti yọ epo ara rẹ̀. | bbc | yo |
BBC kò mọ̀ nípa àwọn ohun tí ó wà ní àwọn ojú òpó tí ó wà ní ìta. | bbc | yo |
Lẹ́yìn tí wọ́n bá sè é tán ni wọn yóo kó o sinu ẹ̀rọ tí yóo lò ó tabi kí wọ́n fi ẹsẹ̀ tẹ̀ẹ́ gẹ́gẹ́ bí wọ́n ti ń ṣe ní ayé àtijọ́ láti yọ epo ara rẹ̀. | bbc | yo |
Orísun àwòrán, Getty Images lọ́sẹ̀ tó kọjá, àjọ ìṣọ̀kan àgbáyé (un) ṣe ìkìlọ̀ nlá wí pé mílíọ̀nù méjìlélọ́gọ́rin àwọn ọmọ Nàìjíríà - nǹkan bíi ìdá mẹ́rìnlélọ́gọ́ta ọmọ Nàìjíríà - ló ṣeé ṣe kí wọ́n kojú ẹbí, kí wọ́n má sì rí nǹkan jẹ mọ́ nígbà tí yóò bá fi di ọdún 2030. | bbc | yo |
Àjọ tó ń rí sí Ìpèsè Oúnjẹ àti Ètò Ọ̀gbìn lagbaye (FAO) nínú àkọsílẹ̀ wọn nípa ìwádìí tí wọ́n ṣe fi hàn pé nígbà tí a ó bá fi rí ọdún díẹ̀ sí àsìkò yìí, wàhálà náà yóò peléke síi lórílẹ̀èdè Nàìjíríà. | bbc | yo |
Àjọ Ìṣọ̀kan Àgbáyé tún ké sí ìjọba orílẹ̀èdè Nàìjíríà láti yanjú ìṣòro àyípadà ojú ọjọ́ àti àwọn ìṣòro kòkòrò tó ń ba èrè oko jẹ́, kí gbogbo wàhálà ohun tó lè dópin. | bbc | yo |
“Èsì àbájáde ìwádìí wa jẹ́ èyí tó ń kọni lóminú, bí mílíọ̀nù méjìlélọ́gọ́rin ni yóò kojú ẹbí ńlá nígbà tí yóò bá fi di ọdún 2030,” wọ̀nyí ni ohun tí taófijúq Braaragu sọ níbi ìpàdé ìdàgbàsókè nípa iṣẹ́ àgbẹ̀ tó wáyé nílùú Àbújá láìpẹ́ yìí.. | bbc | yo |
Lọ́sẹ̀ tó kọjá, Àjọ Ìṣọ̀kan Àgbáyé (UN) ṣe ìkìlọ̀ nlá wí pé mílíọ̀nù méjìlélọ́gọ́rin àwọn ọmọ Nàìjíríà - nǹkan bíi ìdá mẹ́rìnlélọ́gọ́ta ọmọ Nàìjíríà – ló ṣeé ṣe kí wọ́n kojú ẹbí, kí wọ́n má sì rí nǹkan jẹ mọ́ nígbà tí yóò bá fi di ọdún 2030. | bbc | yo |
“Èsì àbájáde ìwádìí wa jẹ́ èyí tó ń kọni lóminú, bí mílíọ̀nù méjìlélọ́gọ́rin ni yóò kojú ẹbí ńlá nígbà tí yóò bá fi di ọdún 2030,” wọ̀nyí ni ohun tí taófijúq Braaragu sọ níbi ìpàdé ìdàgbàsókè nípa iṣẹ́ àgbẹ̀ tó wáyé nílùú Àbújá láìpẹ́ yìí. | bbc | yo |
Bo tilẹ̀ jẹ́ pé wàhálà àìrí oúnjẹ jẹ ti bẹ̀rẹ̀ síí bá àwọn ọmọ Nàìjíríà kan fínra báyìí. | bbc | yo |
Àwọn kan tó bá BBC sọ̀rọ̀ ṣàlàyé nípa bí wọ́n ṣe ń lo gbogbo ọjọ́ wọn láì rí oúnjẹ gidi jẹ.. | bbc | yo |
Àwọn kan tó bá BBC sọ̀rọ̀ ṣàlàyé nípa bí wọ́n ṣe ń lo gbogbo ọjọ́ wọn láì rí oúnjẹ gidi jẹ. | bbc | yo |
Lápá kejì, ìjọba orílẹ̀èdè náà sì bẹ̀rẹ̀ síí gbé àwọn ìgbésẹ̀ mélòó kan, pẹ̀lú èròǹgbà láti ṣàgbẹ̀lárugẹ fún ọ̀rọ̀ iṣẹ́ àgbẹ̀ àti ọ̀gbìn, èyí tí ààrẹ Bólá Tinúbú kéde rẹ̀ lọ́jọ́ Ìṣẹ́gun, ọ̀sẹ̀ yìí, lẹ́yìn tó fi Ìgbìmọ̀ tí yóò ṣiṣẹ́ lábẹ́ rẹ̀ lélẹ̀.. | bbc | yo |
Lápá kejì, ìjọba orílẹ̀èdè náà sì bẹ̀rẹ̀ síí gbé àwọn ìgbésẹ̀ mélòó kan, pẹ̀lú èròńgbà láti ṣàgbẹ̀lárugẹ fún ọ̀rọ̀ iṣẹ́ àgbẹ̀ àti ọ̀gbìn, èyí tí ààrẹ Bólá Tinúbú kéde rẹ̀ lọ́jọ́ Ìṣẹ́gun, ọ̀sẹ̀ yìí, lẹ́yìn tó fi Ìgbìmọ̀ tí yóò ṣiṣẹ́ lábẹ́ rẹ̀ lélẹ̀. | bbc | yo |
Orísun Àwòrán, Ngfmátus Ọ̀mọ̀wé Abubur Sulemanman ni Igbakeji Aare tẹlẹ fun Ajo FAO lórílẹ̀ Nàìjíríà, ó sì ṣàlàyé ọ̀nà márùn-ún tó nílò láti gbà.. | bbc | yo |
Lápá kejì, ìjọba orílẹ̀èdè náà sì bẹ̀rẹ̀ síí gbé àwọn ìgbésẹ̀ mélòó kan, pẹ̀lú èròńgbà láti ṣàgbẹ̀lárugẹ fún ọ̀rọ̀ iṣẹ́ àgbẹ̀ àti ọ̀gbìn, èyí tí ààrẹ Bọ́lá Tinúbú kéde rẹ̀ lọ́jọ́ Ìṣẹ́gun, ọ̀sẹ̀ yìí, lẹ́yìn tó fi Ìgbìmọ̀ tí yóò ṣiṣẹ́ lábẹ́ rẹ̀ lélẹ̀. | bbc | yo |
Orísun Àwòrán, Ngfmátus Ọ̀mọ̀wé Abubur Sulemanman ni Igbakeji Aare tẹlẹ fun Ajo FAO lórílẹ̀ Nàìjíríà, ó sì ṣàlàyé ọ̀nà márùn-ún tó nílò láti gbà. | bbc | yo |
Orísun àwòrán, Getty Images lọ́wọ́lọ́wọ́ báyìí, mílíọ̀nù mọ́kànlélọ́gbọ̀n ni wọ́n ti wà nínú ẹbí Ọ̀gá-fọwọ́-gbóké, gẹ́gẹ́ bí èsì àbájáde ìwádìí Àjọ FAO ṣe sọ.. | bbc | yo |
Orísun àwòrán, Getty Images lọ́wọ́lọ́wọ́ báyìí, mílíọ̀nù mọ́kànlélọ́gbọ̀n ni wọ́n ti wà nínú ẹbí Ọ̀gá-fọwọ́-gbóké, gẹ́gẹ́ bí èsì àbájáde ìwádìí Àjọ FAO ṣe sọ. | bbc | yo |
Àwọn mọ́kànlélọ́gọ́rin èèyàn ni wọ́n ti wà ní bèbè láti má ṣe rí oúnjẹ jẹ mọ́ ní ọdún mẹ́fà sí àsìkò yìí, gẹ́gẹ́ bí àjọ náà tún ṣe kó o jáde.. | bbc | yo |
Ọ̀mọ̀wé Abububu Sulemanman ni igbakeji Aare tele fun ajo FAO lórílẹ̀ Nàìjíríà, ó sì ṣàlàyé ọ̀ná márùn-ún tó nílò láti gbà. | bbc | yo |
Àwọn mọ́kànlélọ́gọ́rin èèyàn ni wọ́n ti wà ní bèbè láti má ṣe rí oúnjẹ jẹ mọ́ ní ọdún mẹ́fà sí àsìkò yìí, gẹ́gẹ́ bí àjọ náà tún ṣe kó o jáde. | bbc | yo |
“Ohun kan gbòógì tó sì fa ohun tó ń ṣẹlẹ̀ yìí ni ètò ọ̀rọ̀ ajé ilẹ̀ Nàìjíríà,” Ọ̀mọ̀wé Sulemanman ló sọ bẹ́ẹ̀. | bbc | yo |
“Bí ọwọ́ oúnjẹ àti àwọn nǹkan lílo míràn ṣe ń lọ sókè ti ṣe ìrànwọ́ gidi.". | bbc | yo |
“Bí owó oúnjẹ àti àwọn nǹkan lílo míràn ṣe ń lọ sókè ti ṣe ìrànwọ́ gidi.” Ó fi kún un pé àlékún lórí owó epo bẹntiróòlù ló fà á tí ọ̀wọ́ àwọn ọjà fi lọ sókè, tó sì ń nira láti rà, nítorí pé gbogbo irè oko pátápátá ni wọ́n ń gbé gba orí ilẹ̀.. | bbc | yo |
Lọ́wọ́lọ́wọ́ báyìí, mílíọ̀nù mọ́kànlélọ́gbọ̀n ni wọ́n ti wà nínú ẹbí Ọ̀gája-fọwọ́-gbóké, gẹ́gẹ́ bí èsì àbájáde ìwádìí Àjọ FAO ṣe sọ. | bbc | yo |
“Bí owó oúnjẹ àti àwọn nǹkan lílo míràn ṣe ń lọ sókè ti ṣe ìrànwọ́ gidi.” Ó fi kún un pé àlékún lórí owó epo bẹntiróòlù ló fà á tí ọ̀wọ́ àwọn ọjà fi lọ sókè, tó sì ń nira láti rà, nítorí pé gbogbo irè oko pátápátá ni wọ́n ń gbé gba orí ilẹ̀. | bbc | yo |
“Wàhálà ètò ààbò náà tún jẹ́ kí àwọn èèyàn sá, tó sì ń jẹ́ kí wọn pàdánù àwọn ọkọ wọn.". | bbc | yo |
“Wàhálà ètò ààbọ̀ náà tún jẹ́ kí àwọn èèyàn sá, tó sì ń jẹ́ kí wọn pàdánù àwọn oko wọn.” Orísun àwòrán, Sulaiman Abubakar. | bbc | yo |
“Wàhálà ètò ààbò náà tún jẹ́ kí àwọn èèyàn sá, tó sì ń jẹ́ kí wọ́n pàdánù àwọn oko wọn.” Orísun àwòrán, Sulaiman Abubakar ọ̀mọ̀wé Abubur Suleman sọ pé àwọn ìgbésẹ̀ kíákíá àti èyí tí yóò jẹ́ ọlọ́jọ́ pípẹ́ wá láti gbé. | bbc | yo |
Ó fi kún un pé àlékún lórí òwò epo bẹntiróòlù ló fà á tí ọ̀wọ́ àwọn ọjà fi lọ sókè, tó sì ń nira láti rà, nítorí pé gbogbo irè oko pátápátá ni wọ́n ń gbé gba orí ilẹ̀. | bbc | yo |
O ṣalaye rẹ lẹ́kùnrẹ́rẹ́ bayii: Akọ́ṣẹ́mọsẹ́ naa sọ pe awọn eeyan kan wa ti wọn ti bori ni ti wọn, to si ni awọn wọnyi ni ajo WFP fi si ipo keji ati ipo kẹta ninu ipele ebi.. | bbc | yo |
O ṣalaye rẹ lẹ́kùnrẹ́rẹ́ bayii: Akọ́ṣẹ́mọsẹ́ naa sọ pe awọn eeyan kan wa ti wọn ti bori ni ti wọn, to si ni awọn wọnyi ni ajo WFP fi si ipo keji ati ipo kẹta ninu ipele ebi. | bbc | yo |
O ní àwọn èèyàn yìí nílò kí wọ́n ràn wọ́n lọ́wọ́ nítorí pé kò síye ohun tí wọ́n lè ṣe láti rí oúnjẹ nítorí pé wọn kò ní ọ̀nà láti mọ̀ bí wọ́n yóò ṣe ríi.. | bbc | yo |
Orisun aworan, Sulaiman Abubakar ọ̀mọ̀wé Abubur Sulemanman sọ pe awọn igbesẹ kiakia ati eyi ti yoo jẹ Olojo pipe wa lati gbe. | bbc | yo |
O ní àwọn èèyàn yìí nílò kí wọ́n ràn wọ́n lọ́wọ́ nítorí pé kò síye ohun tí wọ́n lè ṣe láti rí oúnjẹ nítorí pé wọn kò ní ọ̀nà láti mọ̀ bí wọ́n yóò ṣe ríi. | bbc | yo |
Àwọn èèyàn kò fi bẹ́ẹ̀ dá oko mọ̀, bẹ́ẹ̀ sì ni wọn kò kówó lé orí iṣẹ́ àgbẹ̀ àti ọ̀gbìn mọ́ nítorí wàhálà àti ìṣòro ètò ààbò.. | bbc | yo |
Ọ̀mọ̀wé Abubur Sulemanman sọ pe awọn igbesẹ kiakia ati eyi ti yoo jẹ bayii pipe wa lati gbe. | bbc | yo |
Àwọn èèyàn kò fi bẹ́ẹ̀ dá oko mọ̀, bẹ́ẹ̀ sì ni wọn kò kówó lé orí iṣẹ́ àgbẹ̀ àti ọ̀gbìn mọ́ nítorí wàhálà àti ìṣòro ètò ààbò. | bbc | yo |
Àwọn èèyàn ń dá oko ṣùgbọ́n wọn kò rí èrè níbẹ̀, nítorí pé àwọn ológun ti kó gbogbo ire àti àǹfààní wọn lọ, tàbí ká sọ pé wọ́n nílò láti san owó orí.. | bbc | yo |
Akọ́ṣẹ́mọsẹ́ náà sọ pé àwọn èèyàn kan wà tí wọ́n ti borí ní tí wọ́n, tó sì ní àwọn wọ̀nyí ní àjọ ṣàrún fi sí ipò kejì àti ipò kẹta nínú ìpele ẹbí. | bbc | yo |
Àwọn èèyàn ń dá oko ṣùgbọ́n wọn kò rí èrè níbẹ̀, nítorí pé àwọn ológun ti kó gbogbo ire àti àǹfààní wọn lọ, tàbí ká sọ pé wọ́n nílò láti san owó orí. | bbc | yo |
Àwọn nǹkan wọnyi máa ń fa kí oúnjẹ pọ̀ láti ṣe jáde.. | bbc | yo |
Ó pọn dandan láti mú àyípadà bá ọ̀nà tí à ń gbà láti dá oko, pàápàá jùlọ àwọn oko tí à ń dà sórí ọgbẹ́ ilé àti bi a ṣe ń tọ́jú àwọn irè oko, kí àwọn oúnjẹ má ba à bàjẹ́ níbi tí a bá tọ́jú wọn sí.. | bbc | yo |
Ó pọn dandan láti mú àyípadà bá ọ̀nà tí à ń gbà láti dá oko, pàápàá jùlọ àwọn oko tí à ń dà sórí ọgbẹ́ ilé àti bi a ṣe ń tọ́jú àwọn irè oko, kí àwọn oúnjẹ má ba à bàjẹ́ níbi tí a bá tọ́jú wọn sí. | bbc | yo |
Àwọn èso ìgbàlódé la nílò láti máa ṣe, tí kò wọ́n kò sì ní nílò ọ̀pọ̀ omi.. | bbc | yo |
Àwọn èso ìgbàlódé la nílò láti máa ṣe, tí kò wọ́n kò sì ní nílò ọ̀pọ̀ omi. | bbc | yo |
Ijoba nilo lati se ìrànwọ́ fáwọn agbe kéékèèké nítorí pé àwọn ni igi leyin ogba fun ise agbe ni Naijiria.. | bbc | yo |
Ìjọba nílò láti ṣe ìrànwọ́ fáwọn àgbẹ̀ kéékèèké nítorí pé àwọn ní igi lẹ́yìn ọgbà fún iṣẹ́ àgbẹ̀ ní Nàìjíríà. | bbc | yo |
Kìí ṣe pé ìjọ pé ìjọba kọ́ pèsè ìrànwọ́, wàhálà tó wà níbẹ̀ ni pé kó dé ọ̀dọ̀ àwọn àgbẹ̀ tó wà lórílẹ̀èdè. | bbc | yo |
Orísun Àwòrán, X/Bola Ahmed Tinubu/Agriculture Nigeria kii ṣe iroyin tuntun mo pe Ààrẹ Bola Ahmed Tinubu ti orilẹede Naijiria ti da ẹka ileeṣẹ Ijoba ti yoo maa ri soro awon nnkan ọsin, eyi ti wọn n pe ni 'OyinStock’ sile. | bbc | yo |
Lára àwọn ojúṣe tí iléeṣẹ́ yìí yóò máa bojútó ni bí àlàáfíà àti ìlera pípé yóò ṣe túbọ̀ wà fún àwọn ohun ọ̀sin, pàápàá jùlọ láti paná aáwọ̀ tó n ṣẹlẹ̀ laarin àwọn darandaran àti àwọn àgbẹ̀ nílẹ̀ Nàìjíríà. | bbc | yo |
Ọ̀pọ̀ ìgbà tí kò lọ ń ká ni aáwọ̀ ti bẹ́ sílẹ̀ láàrin àwọn darandaran, pàápàá àwọn Fúlàní darandaran àti àgbẹ̀, tó sì ti mú èmi Dani nípa fífi ẹran jẹ̀kọ. | bbc | yo |
Ìdásílẹ̀ iléeṣẹ́ yìí ni ìjọba àpapọ̀ nígbàgbọ́ pé yóò fi òpin sí gbogbo wàhálà àti ìdúnko náà.. | bbc | yo |
Kìí ṣe ìròyìn tuntun mọ̀ pé ààrẹ Bola Ahmed Tinubu ti orilẹede Naijiria ti dá ẹka iléeṣẹ́ Ìjọba tí yóò maa ri soro àwọn nǹkan ọ̀sìn, èyí tí wọ́n ń pè ní 'LiveStock' sílẹ̀. | bbc | yo |
Ìdásílẹ̀ iléeṣẹ́ yìí ni ìjọba àpapọ̀ nígbàgbọ́ pé yóò fi òpin sí gbogbo wàhálà àti ìdúnko náà. | bbc | yo |
Látìgbà tí ìjọba àpapọ̀ ti kéde ìdásílẹ̀ ẹ̀ka iléeṣẹ́ yìí ni oríṣiríṣi awuyewuye ti ń lọ káàkiri ìgboro. | bbc | yo |
Bí àwọn kan ṣe ń sọ pé ìgbésẹ̀ tó dára ni, bẹ́ẹ̀ làwọn míràn ń sọ pé ohun tó kàn kọ́ lèyí.. | bbc | yo |
Bí àwọn kan ṣe ń sọ pé ìgbésẹ̀ tó dára ni, bẹ́ẹ̀ làwọn míràn ń sọ pé ohun tó kàn kọ́ lèyí. | bbc | yo |
Síbẹ̀, BBC Yorùbá ti wá kan sí àwọn ọ̀jọ̀gbọ́n àti àwọn onímọ̀ ìjìnlẹ̀ nípa iṣẹ́ àgbẹ̀ àti ọ̀gbìn, pàápàá nípa ohun ọ̀sìn nílẹ̀ Áfríkà láti sọ̀rọ̀, oníkálukú wọ́n sì sọ èròńgbà wọn.. | bbc | yo |
Síbẹ̀, BBC Yorùbá ti wá kan sí àwọn ọ̀jọ̀gbọ́n àti àwọn onímọ̀ ìjìnlẹ̀ nípa iṣẹ́ àgbẹ̀ àti ọ̀gbìn, pàápàá nípa ohun ọ̀sìn nílẹ̀ Áfríkà láti sọ̀rọ̀, oníkálukú wọ́n sì sọ èròńgbà wọn. | bbc | yo |
Wọ́n ní ìgbésẹ̀ tó dára ní ìjọba gbé, àti pé yóò mú ìdàgbàsókè bá ètò iṣẹ́ àgbẹ̀ àti ọ̀gbìn, tó fi mọ́ ohun ọ̀sìn.. | bbc | yo |
Wọ́n ní ìgbésẹ̀ tó dára ní ìjọba gbé, àti pé yóò mú ìdàgbàsókè bá ètò iṣẹ́ àgbẹ̀ àti ọ̀gbìn, tó fi mọ́ ohun ọ̀sìn. | bbc | yo |
Ọ̀mọ̀wé Samson Adéọlá Odele tó jẹ́ ògbóǹtarìgì nídi iṣẹ́ àgbẹ̀ àti ọ̀gbìn lórílẹ̀ Nàìjíríà nígbà tó ń ṣàlàyé fún BBC Yorùbá láìló láìpẹ́ yìí, ó ní ìgbéṣẹ́ tó dára ní ìjọba gbé láti láti mú Ìsókè bá ẹ̀ka náà.. | bbc | yo |
Ọ̀mọ̀wé Samson Adéọlá òdeDina tó jẹ́ ògbóǹtarìgì nídi iṣẹ́ àgbẹ̀ àti ọ̀gbìn lórílẹ̀èdè Nàìjíríà nígbà tó ń ṣàlàyé fún BBC Yorùbá láìpẹ́ yìí, ó ní ìgbéṣẹ́ tó dára ní ìjọba àpapọ̀ gbé láti mú ìdàgbà bá ẹ̀ka náà. | bbc | yo |
Ọ̀mọ̀wé Odedínà to je koNàìjíríà ana fòrò eto ise agbe ati ogbin nipinle Ogun so pe ise agbe pin soriwàyí ẹka, gege bi ise Dokita naa se pin soriwàyí ẹka.. | bbc | yo |
Ọ̀mọ̀wé Odedínà to je koNàìjíríà ana fòrò eto ise agbe ati ogbin nipinle Ogun so pe ise agbe pin soriwàyí ẹka, gege bi ise Dokita naa se pin soriwàyí ẹka. | bbc | yo |
“Tí ẹ bá wò ó, iṣẹ́ àgbẹ̀ gbòòrò gidi, bí iṣẹ́ dókítà náà ni. | bbc | yo |
Ní iṣẹ́ dókítà, ẹ máa ṣàkíyèsí pé àwọn dókítà tó ń wo ojú wa, àwọn tí imú wà lọ́tọ̀, àwọn tó ń ṣẹ ẹsẹ̀ náà wà lọ́tọ̀, àti bẹ́ẹ̀bẹ́ẹ̀lọ. | bbc | yo |
“A ti fi ojú tẹmbẹlu iṣẹ́ àgbẹ̀ ni a kò ṣe mọ̀ pé bó ṣe ṣe pàtàkì tó nìyẹn, nítorí pé ohun nìkan la lè ṣe láì gba ìwé àṣẹ dùn ẹ̀.. | bbc | yo |
“A ti fi ojú tẹmbẹlu iṣẹ́ àgbẹ̀ ni a kò ṣe mọ̀ pé bó ṣe ṣe pàtàkì tó nìyẹn, nítorí pé ohun nìkan la lè ṣe láì gba ìwé àṣẹ nìdí ẹ̀. | bbc | yo |
Ní iṣẹ́ àgbẹ̀ yìí, ohun tí ẹlòmíràn gbajúmọ̀ ni ọ̀rọ̀ adìẹ; ẹlòmíràn wà tó jẹ́ pé tòlótòló, àwọn míràn gbajúmọ̀ ẹran àti àwọn nǹkan míràn bẹ́ẹ̀.. | bbc | yo |
Ní iṣẹ́ àgbẹ̀ yìí, ohun tí ẹlòmíràn gbajúmọ̀ ni ọ̀rọ̀ adìẹ; ẹlòmíràn wà tó jẹ́ pé tòlótòló, àwọn míràn gbajúmọ̀ ẹran àti àwọn nǹkan míràn bẹ́ẹ̀. | bbc | yo |
“Àwọn míràn wà tó jẹ́ pé inú ilẹ̀ ni wọ́n ń bá dòwò pọ̀. | bbc | yo |
A rí àwọn ọ̀jọ̀gbọ́n tó jẹ́ pé afẹ́fẹ́ inú ilẹ̀ tí a mọ̀ sí ‘nitrogen’ ni wọ́n ń ṣiṣẹ́ pẹ̀lú.. | bbc | yo |
A rí àwọn ọ̀jọ̀gbọ́n tó jẹ́ pé afẹ́fẹ́ inú ilẹ̀ tí a mọ sí ‘nitrogen’ ni wọ́n ń ṣiṣẹ́ pẹ̀lú. | bbc | yo |
“Ìgbésẹ̀ gidi ni ohun tí ìjọba àpapọ̀ ṣe yìí, nítorí pé ó máa jẹ́ kí ìkọsẹ̀Mose túbọ̀ wọnú iṣẹ́ àgbẹ̀ ni. | bbc | yo |
Tí a bá wò dádàá, ohun ọ̀sìn ṣe pàtàkì gidi ní ìgbésí ayé ẹ̀dá.. | bbc | yo |
Tí a bá wò dádàá, ohun ọ̀sìn ṣe pàtàkì gidi ni ìgbésí ayé ẹ̀dá. | bbc | yo |
“Ìdí ni pé ohun ọ̀sìn dùn lẹ́nu, bẹ́ẹ̀ ló tún kún fún ọpọlọpọ aṣaralóore ti purotéènì, láti orí ẹja, ìgbín, adìẹ, ehoro àti bẹ́ẹ̀bẹ́ẹ̀lọ.. | bbc | yo |
“Ìdí ni pé ohun ọ̀sìn dùn lẹ́nu, bẹ́ẹ̀ ló tún kún fún ọpọlọpọ aṣaralóore ti purotéènì, láti orí ẹja, ìgbín, adìẹ, ehoro àti bẹ́ẹ̀bẹ́ẹ̀lọ. | bbc | yo |
“Ohun tí à ń pè ní liveStock kìí ṣe nípa ohun ọ̀sìn nìkan, oúnjẹ wọn náà ń kó, àwọn oúnjẹ aṣaralóore tí àwọn ohun ọ̀sìn yìí ń jẹ. | bbc | yo |
Nínú gbogbo nǹkan tí a ń gbìn pátápátá, èyí tí ẹranko ń jẹ níbẹ̀ ló pọ̀ jù.. | bbc | yo |
Nínú gbogbo nǹkan tí a ń gbìn pátápátá, èyí tí ẹranko ń jẹ níbẹ̀ ló pọ̀ jù. | bbc | yo |
“Bí ẹ bá wo àgbàdo tí à ń gbìn, ẹranko ati ẹran ọ̀sìn ló ń jẹ èyí tó pọ̀ jù, bẹ́ẹ̀ náà ni sóyà. | bbc | yo |
Gbogbo àwọn ìlànà nípa ohun ọ̀sìn ní àwọn ọmọ wa ń kọ́ nílé ẹ̀kọ́ gíga káàkiri lórílẹ̀èdè Nàìjíríà.. | bbc | yo |
Gbogbo àwọn ìlànà nípa ohun ọ̀sìn ni àwọn ọmọ wa ń kọ́ nílé ẹ̀kọ́ gíga káàkiri lórílẹ̀èdè Nàìjíríà. | bbc | yo |
“Ohun ọ̀sìn kò ṣéé fọwọ́ rọ́ sẹ́yìn nínú iṣẹ́ àgbẹ̀ lágbáyé.". | bbc | yo |
End of preview. Expand
in Dataset Viewer.
README.md exists but content is empty.
Use the Edit dataset card button to edit it.
- Downloads last month
- 43