cleaned_text
stringlengths
6
2.09k
source
stringclasses
2 values
language
stringclasses
1 value
Ọ̀rọ̀ ti àjọ àagbe un gbé jáde yìí ló ń wáyé ní àsìkò tí ọ̀wọ́ngógó oúnjẹ gbòde lórílẹ̀èdè Nàìjíríà, tí ọ̀pọ̀ ilẹ̀ tó sì ní ànfàní láti rí oúnjẹ sí ilẹ̀ bi ti tẹ́lẹ̀ mọ́..
bbc
yo
Ó tẹ̀síwájú pé ìṣòro oúnjẹ tí a ní lórílẹ̀èdè Nàìjíríà ni ó tan mọ́ kùdìẹ̀kudiẹ ojú ọjọ́ àtibí bí kòkòrò ṣe ń fa ọ̀pọ̀ ìjàmbá tó ń wáyé ní ẹ̀ka ọ̀gbìn lórílẹ̀ Nàìjíríà.
bbc
yo
Ọ̀rọ̀ ti àjọ ààgbẹye ún gbé jáde yìí ló n wáyé ní àsìkò ti ọ̀wọ́ngógó oúnjẹ gbòde lórílẹ̀èdè Nàìjíríà, tí ọ̀pọ̀ ilẹ̀ tó sì ní ànfàní lati rí oúnjẹ sí ilẹ̀ bi ti tẹ́lẹ̀ mọ́.
bbc
yo
Bákan náà nínú ìwádìí kan tó jáde síta, ún ní ìdá ogójì tún ti gún orí owó oúnjẹ lórílẹ̀èdè Nàìjíríà, tí èyí sì jẹ́ ohun tí kò ṣẹlẹ̀ rí..
bbc
yo
Bákan náà nínú ìwádìí kan tó jáde síta, ún ní ìdá ogójì tún ti gun orí owó oúnjẹ lórílẹ̀èdè Nàìjíríà, tí èyí sì jẹ́ ohun tí kò ṣẹlẹ̀ rí.
bbc
yo
Lọ́dún tó kọjá, Ààrẹ Bọ́lá Tinúbú kéde ìlú ó fararọ̀ lórí ọ̀rọ̀ náà, nínú ìgbìyànjúláti kó oúnjẹ síta fún aráàlú..
bbc
yo
Lọ́dún tó kọjá, Ààrẹ Bọ́lá Tinúbú kéde ìlú ó fararọ lórí ọ̀rọ̀ náà, nínú ìgbìyànjúláti kó oúnjẹ síta fún aráàlú.
bbc
yo
Láìpẹ́ ni ìjọba tún kéde àwọn ìgbésẹ̀ kan láti ìrọ̀rùn débá nǹkan tí àwọn aráàlú ń là kọjá lásìkò yìí..
bbc
yo
Láìpẹ́ ni ìjọba tún kéde àwọn ìgbésẹ̀ kan láti ìrọ̀rùn débá nǹkan tí àwọn aráàlú ń là kọjá lásìkò yìí.
bbc
yo
Ọ̀kan lára ìgbésẹ̀ ìjọba ni pé ìjọba yóò kó oúnjẹ tó jẹ́ ìwádìífún méjìlógójì síta fún àwọn aráàlú, tí ẹ̀ka ètò ọ̀gbìn yóò ṣe amojú tó rẹ̀..
bbc
yo
Ọ̀kan lára ìgbésẹ̀ ìjọba ni pé ìjọba yóò kó oúnjẹ tó jẹ́ kóo méjìlógójì síta fún àwọn aráàlú, tí ẹ̀ka ètò ọ̀gbìn yóò ṣe amojú tó rẹ.
bbc
yo
Orísun àwòrán, Getty Image ìsọ̀ọ̀ gbajúmọ̀ ní nǹkan jíjẹ́ káàkiri orílẹ̀-èdè yìí.
bbc
yo
Yàtọ̀ sí pé ó dùn lẹ́nu, anfaani ara rẹ̀ fún takọ-tabo tún kọjá à ń dákẹ́ sí.
bbc
yo
Olóyìnbó n pe ẹ ni tiger Nut, ófi ní Yorùbá mọ on sí, Hausa n pè é ní aya, nígbà tí àwọn Igbo ń pè é ní Aki Hausa.
bbc
yo
Lóòótọ́ ni ófió kéré lójú, ṣùgbọ́n àtaré kéré ni, èèyàn kò ní í jẹ́ kóró kan rẹ̀ kó má ta lẹ́nu.
bbc
yo
Bẹ́ẹ̀ ni òfìó náà rí nípa iṣẹ́ rere tó ń ṣe fún ara eniyan.
bbc
yo
Kódà, ohun mímu tí wọ́n fi òfìó ṣe ni àwọn kan gbàgbọ́ pé, ó máa ran ìbálòpọ̀ lọ́wọ́ láàárín takọ-tabo, èyí sì jẹ́ kó di ààyò fún àwọn tó mọ̀ ọ́n..
bbc
yo
Kódà, ohun mímu tí wọ́n fi òfìọ ṣe ni àwọn kan gbàgbọ́ pé, o máa ran ìbálòpọ̀ lọ́wọ́ láàárín takọ-tabo, èyí sì jẹ́ kó di ààyò fún àwọn tó mọ̀ ọ́n.
bbc
yo
Ṣugbọn láìpẹ́ yìí ni ìjọba ẹ̀kọ́ kéde pé kọ́lẹ́rà tó bẹ́ sílẹ̀ lẹ́nu ọjọ́ mẹta yìí kò ṣẹ̀yìn nǹkan mímu tí wọ́n fi òfìó ṣe yìí, èyí tí a mọ̀ sí ‘Tiger nut drink.’
bbc
yo
Ṣugbọn láìpẹ́ yìí ni ìjọba ẹ̀kọ́ kéde pé kọ́lẹ́rà tó bẹ́ sílẹ̀ lẹ́nu ọjọ́ mẹta yìí kò ṣẹ̀yìn nǹkan mímu tí wọ́n fi òfìó ṣe yìí, èyí tí a mọ̀ sí ‘Tiger nut drink.’ Wọ́n ní àwọn kan tí ìmọ́tótó wọn kò ṣéé fẹsẹ̀ ẹ̀ múlẹ̀ nínú àwọn tó ń ṣe é ló fa kọ́lẹ́rà tó gbòde..
bbc
yo
Ṣugbọn láìpẹ́ yìí ni ìjọba ẹ̀kọ́ kéde pé kọ́lẹ́rà tó bẹ́ sílẹ̀ lẹ́nu ọjọ́ mẹta yìí kò ṣẹ̀yìn nǹkan mímu tí wọ́n fi òfìó ṣe yìí, èyí tí a mọ̀ sí ‘Tiger nut drink.’ Wọ́n ní àwọn kan tí ìmọ́tótó wọn kò ṣéé fẹsẹ̀ ẹ̀ múlẹ̀ nínú àwọn tó ń ṣe é ló fa kọ́lẹ́rà tó gbòde.
bbc
yo
Ìkéde yìí ti mú ọ̀pọ̀ èèyàn ṣọ́ra fún nǹkan mímu olófìọ, ṣùgbọ́n bí kò bá sí èyí, ófi gbayì l’Afrika, apá kan àsìá àti orílẹ̀èdè Spain..
bbc
yo
Ìkéde yìí ti mú ọ̀pọ̀ èèyàn ṣọ́ra fún nǹkan mímu olófìọ, ṣùgbọ́n bí kò bá sí èyí, ófi gbayì l’Afrika, apá kan àsìá àti orílẹ̀èdè Spain.
bbc
yo
Látilẹ̀, oṣéò kì í ṣe èso oníkóró, ẹ̀yà oúnjẹ tí wọ́n máa ń wá bíi iṣu ni, bó tilẹ̀ jẹ́ pé wọn kì í tóbi bíi iṣu.
bbc
yo
Àwọn èèyàn yóo máa tú fùlùfúlù tó bá jáde nígbà tí wọ́n bá ń jẹ ẹ́ nù, wọn kì í gbé e mì..
bbc
yo
Wọ́n ní àwọn kan tí ìmọ́tótó wọn kò ṣeé fẹsẹ̀ ẹ̀ múlẹ̀ nínú àwọn tó ń ṣe é ló fa kọ́lẹ́rà tó gbòde.
bbc
yo
Àwọn èèyàn yóo máa tú fùlùfúlù tó bá jáde nígbà tí wọn bá ń jẹ ẹ́ nù, wọn kì í gbé e mì.
bbc
yo
Ọ̀mọ̀wé Abosede Olówóku, ẹni tó gboyè nípa ìwádìí oògùn àti àwọn nǹkan tí Olúwa dá, ṣàlàyé fún BBC pé “Irúgbìn tí a máa ń wà nílé bíi iṣu àti ẹ̀pà ní òfìo.".
bbc
yo
Ọ̀mọ̀wé àbòsede Olowoku, ẹni tó gboyè nípa ìwádìí oògùn àti àwọn nǹkan tí Olúwa dá, ṣàlàyé fún BBC pé “Irúgbìn tí a máa ń wà nílé bíi iṣu àti ẹ̀pà ní òfìo.” Ọ̀mọ̀wé Olówóku ṣàlàyé pé àǹfààní ìlera tó wà nínú nǹkan mímu tí wọ́n fi òfìò ṣe ju ti kúnu lọ..
bbc
yo
Ọ̀mọ̀wé àbòsede Olowoku, ẹni tó gboyè nípa ìwádìí oògùn àti àwọn nǹkan tí Olúwa dá, ṣàlàyé fún BBC pé “Irúgbìn tí a máa ń wà nílé bíi iṣu àti ẹ̀pà ní òfìo.” Ọ̀mọ̀wé Olówóku ṣàlàyé pé àǹfààní ìlera tó wà nínú nǹkan mímu tí wọ́n fi òfìò ṣe ju ti kúnu lọ.
bbc
yo
Ó ní ìyẹn ló ṣe jẹ́ pé ohun mímu olófìo ti lè kúnu mímu lọ́jà, tó jẹ́ òun làwọn èèyàn ń bèèrè fún jùlọ kí kọ́lẹ́rà tóó dé..
bbc
yo
Ó ní ìyẹn ló ṣe jẹ́ pé ohun mímu olófìó ti lè kúnu mímu lọ́jà, tó jẹ́ òun làwọn èèyàn ń bèèrè fún jùlọ kí kọ́lẹ́rà tóó dé.
bbc
yo
“Èròjà protein ati fítámì pọ̀ ninu nǹkan mímu tí a fi òfìo ṣe, bẹ́ẹ̀ làwọn mi-ín ń lò fún kí ara wọn fi jí pépé nítorí ìbálòpọ̀..
bbc
yo
“Èròjà protein ati fítámì pọ̀ ninu nǹkan mímu tí a fi òfìo ṣe, bẹ́ẹ̀ làwọn mi-ín ń lò fún kí ara wọn fi jí pépé nítorí ìbálòpọ̀.
bbc
yo
''Tí ó bá po òfìó pọ̀ mọ́ dàbínù, ohun tí a gbọ́ ni pé ó máa ṣe àlèẹkún agbára ìbálòpọ̀, ṣùgbọ́n èmi ó tí ì wádìí débẹ̀ yẹn ṣáá..
bbc
yo
Ọ̀mọ̀wé Olówófo ṣàlàyé pé àǹfààní ìlera tó wà nínú nǹkan mímu tí wọ́n fi òfìo ṣe ju ti kúnu lọ.
bbc
yo
''Tí ó bá po òfìó pọ̀ mọ́ dàbínù, ohun tí a gbọ́ ni pé ó máa ṣe àlèẹkún agbára ìbálòpọ̀, ṣùgbọ́n èmi ò tí ì wádìí débẹ̀ yẹn ṣáá.
bbc
yo
''Ṣùgbọ́n ohun tí mo fẹ́ràn púpọ̀ lára òfìó ni pé ó jẹ́ ọ̀nà kan láti rí èròjà protein púpọ̀, bẹ́ẹ̀ ló sì tún ní àwọn èròjà mi-ín tí à ń pè ní mínírà pẹ̀lú fítámìn nínú.".
bbc
yo
''Ṣùgbọ́n ohun tí mo fẹ́ràn púpọ̀ lára ọ̀rúgbìn ni pé ó jẹ́ ọ̀nà kan láti rí èròjà protein púpọ̀, bẹ́ẹ̀ ló sì tún ní àwọn èròjà mi-in tí a ń pè ní mínírà pẹ̀lú fítámìn nínú." Bákan náà, Juliana OsaKue tó ti kẹ́kọ̀ọ́ nípa fífi ewé àti egbò ṣe ìwòsàn, sọ pé ófi ó ń ṣiṣẹ́ gidi téèyàn bá lò ó bó ṣe yẹ kó lò ó fún ìwòsàn..
bbc
yo
''Ṣùgbọ́n ohun tí mo fẹ́ràn púpọ̀ lára ọ̀rúgbìn ni pé ó jẹ́ ọ̀nà kan láti rí èròjà protein púpọ̀, bẹ́ẹ̀ ló sì tún ní àwọn èròjà mi-in tí a ń pè ní mínírà pẹ̀lú fítámìn nínú." Bákan náà, Juliana OsaKue tó ti kẹ́kọ̀ọ́ nípa fífi ewé àti egbò ṣe ìwòsàn, sọ pé ófi ó ń ṣiṣẹ́ gidi téèyàn bá lò ó bó ṣe yẹ kó lò ó fún ìwòsàn.
bbc
yo
Ìyá náà sọ pé pàápàá lábala àìṣedè níbi ìbálòpọ̀ ọkùnrin àti obìnrin.
bbc
yo
Ó ní kò sì ní í ṣe èèyàn ní jàm̀bá kankan rárá Lẹ́yìn lílo náà ( Zero sí Effe)..
bbc
yo
O ní kò sí ní í ṣe èèyàn ní jamba kankan rárá lẹ́yìn lílò náà ( Zero side effect).
bbc
yo
Orísun àwòrán, Getty Image wọn ni bí o bá ti rẹ ófi rẹ̀ sínú omi mọ́jú, tí o fi àgbọn àti dàbínù sí i, èyí tó kù ni kí ó lò ó lérò..
bbc
yo
Bákan náà, Juliana OsaKue to ti kẹ́kọ̀ọ́ nípa fífi ewé àti egbò ṣe ìwòsàn, sọ pé ófió ń ṣiṣẹ́ gidi téèyàn bá lò ó bó ṣe yẹ kó lò ó fún ìwòsàn.
bbc
yo
Orísun àwòrán, Getty Image wọn ni bí o bá ti rẹ òfìo rẹ̀ sínú omi mọ́jú, tí o fi àgbọn àti dàbínù sí i, èyí tó kù ni kí o lò ó lérò.
bbc
yo
Lẹ́yìn èyí, fi àṣẹ ṣe é láti yọ omi kúrò lára fùlùfúlù.
bbc
yo
Àwọn mi-ín máa ń fi ata ilẹ̀ (IGIGger) sí i láti jẹ́ kó ta lẹ́nu kò sí ṣiṣẹ́ dáadáa.
bbc
yo
Ṣùgbọ́n àwọn èèyàn mi-in kì í fi ata ilẹ̀ sí tiwọn rárá..
bbc
yo
Ṣùgbọ́n àwọn èèyàn mi-ín kì í fi ata ilẹ̀ sí tiwọn rárá.
bbc
yo
Nínú àmọ̀ràn ọ̀mọ̀wé Olówófo, ó ní kí àwọn tí ófiré kó bá bá lára mu jìnnà sí i, nítorí àwọn èèyàn kan wà tí wọ́n máa ń kojú àwọn àyípadà lára wọn bí wọ́n bá jẹ nǹkan kan tí kò bá wọn lára mu..
bbc
yo
Wọ́n ní bí o bá ti rẹ òfìọ rẹ sínú omi mọ́jú, tí o fi àgbọn àti dàbínù sí i, èyí tó kù ni kí o lò ó lérò.
bbc
yo
Nínú àmọ̀ràn ọ̀mọ̀wé àìsayékù, ó ní kí àwọn tí ófió kó bá bá lára mu jìnnà sí i, nítorí àwọn èèyàn kan wà tí wọ́n máa ń kojú àwọn àyípadà lára wọn bí wọ́n bá jẹ nǹkan kan tí kò bá wọn lára mu.
bbc
yo
Ó ní ṣùgbọ́n òun kò rí wàhálà kankan pẹ̀lú mímú nǹkan mímu tí wọ́n fi lígbẹnu ṣe .
bbc
yo
Àfi àwọn tí wọ́n máa ń fi ṣúgà púpọ̀ ba ayé nǹkan mímu náà jẹ́..
bbc
yo
Àfi àwọn tí wọ́n máa ń fi ṣúgà púpọ̀ ba ayé nǹkan mímu náà jẹ́.
bbc
yo
Ó ní èyí kò dáa fáwọn tí wọ́n bá ní ìtọ̀ ṣúgà, nítorí dàbínù tó wà nínú Tiger Nut ti ní ṣúgà tó pọ̀ lára ní tiẹ̀ tẹ́lẹ̀..
bbc
yo
Ó ní èyí kò dáa fáwọn tí wọ́n bá ní ìtọ̀ ṣúgà, nítorí dàbínù tó wà nínú Tiger Nut ti ní ṣúgà tó pọ̀ lára ní tiẹ̀ tẹ́lẹ̀.
bbc
yo
Orísun àwòrán, Getty Image ọ̀mọ̀wé Olówófokù ka àwọn nǹkan wọ̀nyí bíi àǹfààní tó wà nínú òfio:.
bbc
yo
Orísun àwòrán, Getty Image ọ̀mọ̀wé Olówófòyekù ka àwọn nǹkan wọ̀nyí bíi àǹfààní tó wà nínú ọ̀rúgbìn: gbígbógun ti àìlè ṣe ìgbọ̀nsẹ̀ nírọ̀rùn.
bbc
yo
Orísun àwòrán, Getty Image Ọ̀mọ̀wé Olówófokù ka àwọn nǹkan wọ̀nyí bíi àǹfààní tó wà nínú Òfìo: Gbígbógun ti àìlè ṣe ìgbọ̀nsẹ̀ nírọ̀rùn ó máa ń gbógun ti ai lè ṣe igbóṣe nírọ̀rùn nítorí èròjà protein àti fib tó wà nínú rẹ̀..
bbc
yo
Orísun àwòrán, Getty Image Ọ̀mọ̀wé Olówófokù ka àwọn nǹkan wọ̀nyí bíi àǹfààní tó wà nínú Òfìo: Gbígbógun ti àìlè ṣe ìgbọ̀nsẹ̀ nírọ̀rùn ó máa ń gbógun ti ai lè ṣe igbóṣe nírọ̀rùn nítorí èròjà protein àti fib tó wà nínú rẹ̀.
bbc
yo
Àkọsílẹ̀ kan tó wá láti ‘National Center for Biotechnology information’ sọ pé òfìo ní èròjà fib tó pọ̀ ju ti àwọn oúnjẹ mi-in lọ..
bbc
yo
Ọ̀mọ̀wé olówófokù ká àwọn nǹkan wọ̀nyí bíi anfaani tó wà ninu ófi:o: gbígbógun ti àìlè ṣe ìgbọ̀nsẹ̀ nirọrùn ó máa ń gbógun ti àì lè ṣe igbóṣe nírọ̀rùn nítorí èròjà protein àti fib tó wà nínú rẹ̀.
bbc
yo
Àkọsílẹ̀ kan tó wá láti ‘National center for Biotechnology information’ sọ pé òfìó ní èròjà fibre tó pọ̀ ju ti àwọn oúnjẹ mi-in lọ.
bbc
yo
Ìwádìí fi hàn pé àwọn oúnjẹ tí wọ́n bá kún fún èròjà fib máa ń dènà jẹjẹrẹ ìfun, àìlè ṣe ìgbọ̀nsẹ̀ dáadáa, ará ṣíṣàn asánjù àti àìsàn ọkàn..
bbc
yo
Gbígbógun ti àìlè ṣe ìgbọ̀nsẹ̀ nírọ̀rùn o máa ń gbógun ti ai lè ṣe igbóṣe nírọ̀rùn nítorí èròjà protein àti fiBre tó wà nínú rẹ̀.
bbc
yo
Ìwádìí fi hàn pé àwọn oúnjẹ tí wọ́n bá kún fún èròjà fib máa ń dènà jẹjẹrẹ ìfun, àìlè ṣe ìgbọ̀nsẹ̀ dáadáa, ará ṣíṣàn asánjù ati àìsàn ọkàn.
bbc
yo
Ó máa ń gbógun ti àì lè ṣe igbóṣe nírọ̀rùn nítorí èròjà protein àti fib tó wà nínú rẹ̀.
bbc
yo
Ìtọ̀ ṣúgà fún àwọn èèyàn tí wọ́n ní àìsàn ìtọ̀ ṣúgà, ó dáa kí wọ́n mú ohun mímu olófìọ tiwọn bẹ́ẹ̀ láì fi adùn kankan sí i..
bbc
yo
Ìtọ̀ ṣúgà fún àwọn èèyàn tí wọ́n ní àìsàn ìtọ̀ ṣúgà, ó dáa kí wọ́n mú ohun mímu olófìó tiwọn bẹ́ẹ̀ láì fi adùn kankan sí i.
bbc
yo
Ó ní ìwé kan,‘International Journal of Diabetes in Developing Countries’ tí wọ́n gbé jáde ní 2015, ṣàlàyé pé ó dáa káwọn èèyàn tí wọ́n ní ìtọ̀ ṣúgà oríṣi kejì (type 2 Diabetes) máa jẹ́ òfio, nítorí ó máa ń ṣàtúnṣe sí bí ṣúgà yóò ṣe pọ̀ tó nínú ẹ̀jẹ̀ wọn..
bbc
yo
Ó ní ìwé kan,‘International Journal of Diabetes in Developing Countries’ tí wọ́n gbé jáde ní 2015, ṣàlàyé pé ó dáa káwọn èèyàn tí wọ́n ní ìtọ̀ ṣúgà oríṣi kejì (type 2 Diabetes) máa jẹ́ òfio, nítorí ó máa ń ṣàtúnṣe sí bí ṣúgà yóò ṣe pọ̀ tó nínú ẹ̀jẹ̀ wọn.
bbc
yo
Òfìo tún ṣeé rọ́pò mílíìkì bí Olówófo ṣe ṣàlàyé..
bbc
yo
Fún àwọn èèyàn tí wọ́n ní àìsàn ìtọ̀ ṣúgà, ó dáa kí wọ́n mú ohun mímu olófìọ tiwọn bẹ́ẹ̀ láì fi adùn kankan sí i.
bbc
yo
''Tí ò bá mú ohun mímu tí a fi òfìo ṣe, ìnira tó máa ń bá àwọn ẹlòmí-in bí wọ́n bá mu mílíkì gangan kò ní í sọ ọ́ wò rárá.
bbc
yo
“ ''National center for ! Information’’ naa sọ ninu ọ̀rọ̀ àpilẹ̀kọ wọn kan, pé òfìo tún wúlò fáwọn tí wọn ń se ohun jíjẹ bíi burẹdi, òróró wà lára rẹ̀ bí wọ́n ṣe wí, ó sì le di màkàrónì (Tiger Nut pasta)..
bbc
yo
“ ''National center for ! Information’’ naa sọ ninu ọ̀rọ̀ àpilẹ̀kọ wọn kan, pé òfìo tún wúlò fáwọn tí wọn ń se ohun jíjẹ bíi burẹdi, òróró wà lára rẹ̀ bí wọ́n ṣe wí, ó sì le di màkàrónì (Tiger Nut pastata).
bbc
yo
''National Center for Saúl information’’ náà sọ ninu ọ̀rọ̀ àpilẹ̀kọ wọn kan, pé òfio tún wúlò fáwọn tí wọn ń ṣe ohun jíjẹ bíi burẹdi, òróró wà lára rẹ̀ bí wọ́n ṣe wí, ó sì lè di màkàrónì (Tiger Nut pastata).
bbc
yo
Àwọn ọmọdé ló ń ṣa àwọn èròjà tí àwọn alágbàtà iléeṣẹ́ aṣaralóge ńláńlá méjì kan ń lò láti tà fún wọn fi ṣe ọjà wọn.
bbc
yo
Ìwádìí BBC lórí àwọn ìlànà tí àwọn iléeṣẹ́ kan fi ń ṣe àwọn èròjà aṣaralóge Olorundidun ti wọ́n n ta fihàn pé àwọn ọmọdé ni wọ́n fi n ṣe iṣẹ́ ẹrú lati ṣa èròjà Jasmine ti àwọn alágbàtà Lanmet àti aerin beauty nlo kó fún àwọn iléeṣẹ́ ti wn ń bá ṣiṣẹ́.
bbc
yo
Gbogbo àwọn iléeṣẹ́ tó ń ṣe àwọn èròjà aṣaralóge ọlọ́rundídùn ni wọ́n máa ń sọ pé àwọn kò fi ayé gba lílo àwọn ọmọ fi ṣiṣẹ́ lọ́nà tí kò egungun.
bbc
yo
L'Oreal, to ni awọn aṣaralóge Olorundídùn Lanmet ni awọn ko fi ọrọ ẹ̀tọ́ ọmọnìyàn ṣere rara.
bbc
yo
ESẹ lauder to ní àwọn èròjà aṣaralóge Olorundídùn aerin beauty ni àwọn ti kàn sí àwọn alágbàtà àwọn.
bbc
yo
Gbogbo àwọn iléeṣẹ́ tó ń ṣe àwọn èròjà aṣaralóge ọlọ́rundídùn ni wọ́n máa ń sọ pé àwọn kò fi ayé gba lílo àwọn ọmọ fi ṣiṣẹ́ lọ́nà tí kò egungunnígbà.
bbc
yo
L'Oreal, to ni awọn aṣaralóge Olorundidun Lanmet ni awọn ko fi ọrọ ẹtọ ọmọnìyàn ṣere rara.
bbc
yo
Orísun àwòrán, Getty Images nínú ọ̀rọ̀ àkọ́sọ Bọ́lá Tinúbú sí àwọn ọmọ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà lẹ́yìn tí wọ́n búra fún-un tán gẹ́gẹ́ bí Ààrẹ ló ti kéde pé kò ní ìrànwọ́ tí ìjọba lórí ọwọ́ bẹntiróòlù mọ́.
bbc
yo
Ìrànwọ́ Orí epo bẹntiróòlù “subsípò” ní èdè Gẹ̀ẹ́sì ní owó tí ìjọba máa ń san fún àwọn lá’gbáta tó ń gbé epo wọ Nàìjíríà láti òkè òkun láti lè jẹ́ kí wọ́n máa ta epo ní àdínkù sí iye tí wọ́n ń rà á.
bbc
yo
Òbítíbitì owó ni ìjọba máa ń ná láti fi ṣe ìrànwọ́ yìí ni ọdọọdún tí àwọn onímọ̀ kan láti ọjọ́ pípẹ́ sí ti ni kí ìjọba dá dúró.
bbc
yo
Bẹ́ẹ̀ náà ni àwọn mìíràn wòye pé kò yẹ kí ìjọba yọ ìrànwọ́ yìí nítorí ohun ni àǹfàní ìjọba tí àwọn ará ìlú ń jẹ jùlọ àti pé yóò mú ìpalára bá àwọn ènìyàn tí ìjọba kò bá ṣe é mọ́..
bbc
yo
Nínú ọ̀rọ̀ àkọ́sọ Bọ́lá Tinúbú sí àwọn ọmọ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà lẹ́yìn tí wọ́n búra fún-un tán gẹ́gẹ́ bí Ààrẹ ló ti kéde pé kò ní ìrànwọ́ tí ìjọba lórí ọwọ́ bẹntiróòlù mọ́.
bbc
yo
Bẹ́ẹ̀ náà ni àwọn mìíràn wòye pé kò yẹ kí ìjọba yọ ìrànwọ́ yìí nítorí ohun ni ànfàní ìjọba tí àwọn ará ìlú ń jẹ jùlọ ati pé yóo mú ìpalára bá àwọn eniyan tí ìjọba kò bá ṣe é mọ́.
bbc
yo
Lẹ́yìn-ọ̀-rẹyìn, Tinúbú kéde pé kò ní sí ìrànwọ́ náà mọ́ lọ́jọ́ tí wọ́n búra wọlé fún..
bbc
yo
Lẹ́yìn-ọ̀-rẹyìn, Tinúbú kéde pé kò ní sí ìrànwọ́ náà mọ́ lọ́jọ́ tí wọ́n búra wọlé fún.
bbc
yo
Èyí mú kí ọwọ́ epo bẹntiróòlù lọ sókè láti ń185 jálá kan di iye tó lé ní n300 jálá kan..
bbc
yo
Èyí mú kí ọwọ́ epo bẹntiróòlù lọ sókè láti ń185 jálá kan di iye tó lé ní n300 jálá kan.
bbc
yo
Ní báyìí, iye tí wọ́n ń ta jálá epo bẹntiróòlù wà láàárín ń568 sí N1,000 káàkiri Nàìjíríà..
bbc
yo
Ní báyìí, iye tí wọ́n ń ta jálá epo bẹntiróòlù wà láàárín ń568 sí N1,000 káàkiri Nàìjíríà.
bbc
yo
Àmọ́ àwọn onímọ̀ kan kò gbà pé ìjọba kò san ìrànwọ́ orí epo bẹntiróòlù mọ́ nítorí wọ́n gbàgbọ́ pé iye i wọn sì ń ta epo kéré sí iye tí wọ́n fi ń gbé wọlé lọ..
bbc
yo
Àmọ́ àwọn onímọ̀ kan kò gbà pé ìjọba kò san ìrànwọ́ orí epo bẹntiróòlù mọ́ nítorí wọ́n gbàgbọ́ pé iye i wọn sì ń ta epo kéré sí iye tí wọ́n fi ń gbé wọlé lọ.
bbc
yo