text
stringlengths 44
22.5k
| language
stringclasses 1
value | source
stringclasses 2
values |
---|---|---|
Lode oni, epo pupa ni ohun isebe ti gbogbo agbaye n je ju lo. | yo | bbc |
Iroyin inu fidio yii se ayewo bi won ti se maa n se epo, ibi ti o ti n wa ati bi o se n gbera so di ohun adidudn inu obe. | yo | bbc |
Orisun aworan, Getty Images Ara eso eyin ti won ko lori igi ope ni won ti maa n ri epo pupa. | yo | bbc |
Ekun iwo oorun Afirika ni igi ope wule ti gbile, amosa lode oni o ti kaakairi awon ile olooru lagbaye lati lee koju bi awon eeyan se n fe e si. | yo | bbc |
Idi eyin ti won ba ko lori igi ope wonyii ni won yoo ko lo si ibi ti won yoo ti se e, tabi lo si ileese ti won ti n se epo pupa. | yo | bbc |
Nibe ni won yoo ti yo awon eyin wonyii kuro lara idi eyin ti won ko bo lati oko.. | yo | bbc |
Iroyin inu fidio yii se ayewo bi won ti se maa n se epo, ibi ti o ti n wa ati bi o se n gbera so di ohun adidudn inu obe. | yo | bbc |
Orisun aworan, Getty Images Ara eso eyin ti won ko lori igi ope ni won ti maa n ri epo pupa. | yo | bbc |
Ekun iwo oorun Afirika ni igi ope wule ti gbile, amosa lode oni o ti kaakairi awon ile olooru lagbaye lati lee koju bi awon eeyan se n fe e si. | yo | bbc |
Idi eyin ti won ba ko lori igi ope wonyii ni won yoo ko lo si ibi ti won yoo ti se e, tabi lo si ileese ti won ti n se epo pupa. | yo | bbc |
Nibe ni won yoo ti yo awon eyin wonyii kuro lara idi eyin ti won ko bo lati oko. | yo | bbc |
Ni kete ti won ba yo eyin yii tan ni won yoo daa si inu ikoko ti won yoo fi se e ti won yoo si dana sii labe.. | yo | bbc |
Orisun aworan, Getty Images Ara eso eyin ti won ko lori igi ope ni won ti maa n ri epo pupa. | yo | bbc |
Ekun iwo oorun Afirika ni igi ope wule ti gbile, amosa lode oni o ti kaakairi awon ile olooru lagbaye lati lee koju bi awon eeyan se n fe e si. | yo | bbc |
Idi eyin ti won ba ko lori igi ope wonyii ni won yoo ko lo si ibi ti won yoo ti se e, tabi lo si ileese ti won ti n se epo pupa. | yo | bbc |
Nibe ni won yoo ti yo awon eyin wonyii kuro lara idi eyin ti won ko bo lati oko. | yo | bbc |
Ni kete ti won ba yo eyin yii tan ni won yoo daa si inu ikoko ti won yoo fi se e ti won yoo si dana sii labe. | yo | bbc |
Leyin ti won ba se e tan ni won yoo ko o sinu ero ti yoo lo o tabi ki won fi ese tee gege bi won ti n se ni aye atijo lati yo epo ara re.. | yo | bbc |
Ara eso eyin ti won ko lori igi ope ni won ti maa n ri epo pupa. | yo | bbc |
Ekun iwo oorun Afirika ni igi ope wule ti gbile, amosa lode oni o ti kaakairi awon ile olooru lagbaye lati lee koju bi awon eeyan se n fe e si. | yo | bbc |
Idi eyin ti won ba ko lori igi ope wonyii ni won yoo ko lo si ibi ti won yoo ti se e, tabi lo si ileese ti won ti n se epo pupa. | yo | bbc |
Nibe ni won yoo ti yo awon eyin wonyii kuro lara idi eyin ti won ko bo lati oko. | yo | bbc |
Ni kete ti won ba yo eyin yii tan ni won yoo daa si inu ikoko ti won yoo fi se e ti won yoo si dana sii labe. | yo | bbc |
Leyin ti won ba se e tan ni won yoo ko o sinu ero ti yoo lo o tabi ki won fi ese tee gege bi won ti n se ni aye atijo lati yo epo ara re. | yo | bbc |
BBC ko mo nipa awon ohun ti o wa ni awon oju opo ti o wa ni ita. | yo | bbc |

Orisun aworan, Getty Images Lose to koja, ajo isokan agbaye (UN) se ikilo nla wi pe milionu mejilelogorin awon omo Naijiria - nnkan bii ida merinlelogota omo Naijiria - lo see se ki won koju ebi, ki won ma si ri nnkan je mo nigba ti yoo ba fi di odun 2030. | yo | bbc |
Ajo to n ri si ipese ounje ati eto ogbin lagbaye (FAO) ninu akosile won nipa iwadii ti won se fi han pe nigba ti a o ba fi ri odun die si asiko yii, wahala naa yoo peleke sii lorileede Naijiria. | yo | bbc |
Ajo isokan agbaye tun ke si ijoba orileede Naijiria lati yanju isoro ayipada oju ojo ati awon isoro kokoro to n ba ere oko je, ki gbogbo wahala ohun to le dopin. | yo | bbc |
"Esi abajade iwadii wa je eyi to n koni lominu, bi milionu mejilelogorin ni yoo koju ebi nla nigba ti yoo ba fi di odun 2030," wonyi ni ohun ti Taofiq Braimoh so nibi ipade idagbasoke nipa ise agbe to waye niluu Abuja laipe yii.. | yo | bbc |
Lose to koja, ajo isokan agbaye (UN) se ikilo nla wi pe milionu mejilelogorin awon omo Naijiria - nnkan bii ida merinlelogota omo Naijiria - lo see se ki won koju ebi, ki won ma si ri nnkan je mo nigba ti yoo ba fi di odun 2030. | yo | bbc |
Ajo to n ri si ipese ounje ati eto ogbin lagbaye (FAO) ninu akosile won nipa iwadii ti won se fi han pe nigba ti a o ba fi ri odun die si asiko yii, wahala naa yoo peleke sii lorileede Naijiria. | yo | bbc |
Ajo isokan agbaye tun ke si ijoba orileede Naijiria lati yanju isoro ayipada oju ojo ati awon isoro kokoro to n ba ere oko je, ki gbogbo wahala ohun to le dopin. | yo | bbc |
"Esi abajade iwadii wa je eyi to n koni lominu, bi milionu mejilelogorin ni yoo koju ebi nla nigba ti yoo ba fi di odun 2030," wonyi ni ohun ti Taofiq Braimoh so nibi ipade idagbasoke nipa ise agbe to waye niluu Abuja laipe yii. | yo | bbc |
Bo tile je pe wahala airi ounje je ti bere sii ba awon omo Naijiria kan finra bayii. | yo | bbc |
Awon kan to ba BBC soro salaye nipa bi won se n lo gbogbo ojo won lai ri ounje gidi je.. | yo | bbc |
Ajo to n ri si ipese ounje ati eto ogbin lagbaye (FAO) ninu akosile won nipa iwadii ti won se fi han pe nigba ti a o ba fi ri odun die si asiko yii, wahala naa yoo peleke sii lorileede Naijiria. | yo | bbc |
Ajo isokan agbaye tun ke si ijoba orileede Naijiria lati yanju isoro ayipada oju ojo ati awon isoro kokoro to n ba ere oko je, ki gbogbo wahala ohun to le dopin. | yo | bbc |
"Esi abajade iwadii wa je eyi to n koni lominu, bi milionu mejilelogorin ni yoo koju ebi nla nigba ti yoo ba fi di odun 2030," wonyi ni ohun ti Taofiq Braimoh so nibi ipade idagbasoke nipa ise agbe to waye niluu Abuja laipe yii. | yo | bbc |
Bo tile je pe wahala airi ounje je ti bere sii ba awon omo Naijiria kan finra bayii. | yo | bbc |
Awon kan to ba BBC soro salaye nipa bi won se n lo gbogbo ojo won lai ri ounje gidi je. | yo | bbc |
Lapa keji, ijoba orileede naa si bere sii gbe awon igbese meloo kan, pelu erongba lati sagbelaruge fun oro ise agbe ati ogbin, eyi ti Aare Bola Tinubu kede re lojo Isegun, ose yii, leyin to fi igbimo ti yoo sise labe re lele.. | yo | bbc |
Ajo isokan agbaye tun ke si ijoba orileede Naijiria lati yanju isoro ayipada oju ojo ati awon isoro kokoro to n ba ere oko je, ki gbogbo wahala ohun to le dopin. | yo | bbc |
"Esi abajade iwadii wa je eyi to n koni lominu, bi milionu mejilelogorin ni yoo koju ebi nla nigba ti yoo ba fi di odun 2030," wonyi ni ohun ti Taofiq Braimoh so nibi ipade idagbasoke nipa ise agbe to waye niluu Abuja laipe yii. | yo | bbc |
Bo tile je pe wahala airi ounje je ti bere sii ba awon omo Naijiria kan finra bayii. | yo | bbc |
Awon kan to ba BBC soro salaye nipa bi won se n lo gbogbo ojo won lai ri ounje gidi je. | yo | bbc |
Lapa keji, ijoba orileede naa si bere sii gbe awon igbese meloo kan, pelu erongba lati sagbelaruge fun oro ise agbe ati ogbin, eyi ti Aare Bola Tinubu kede re lojo Isegun, ose yii, leyin to fi igbimo ti yoo sise labe re lele. | yo | bbc |

Orisun aworan, NGFMAFS Omowe Abubukar Suleiman ni igbakeji aare tele fun ajo FAO lorileede Naijiria, o si salaye ona marun-un to nilo lati gba.. | yo | bbc |
Bo tile je pe wahala airi ounje je ti bere sii ba awon omo Naijiria kan finra bayii. | yo | bbc |
Awon kan to ba BBC soro salaye nipa bi won se n lo gbogbo ojo won lai ri ounje gidi je. | yo | bbc |
Lapa keji, ijoba orileede naa si bere sii gbe awon igbese meloo kan, pelu erongba lati sagbelaruge fun oro ise agbe ati ogbin, eyi ti Aare Bola Tinubu kede re lojo Isegun, ose yii, leyin to fi igbimo ti yoo sise labe re lele. | yo | bbc |
Orisun aworan, NGFMAFS Omowe Abubukar Suleiman ni igbakeji aare tele fun ajo FAO lorileede Naijiria, o si salaye ona marun-un to nilo lati gba. | yo | bbc |

Orisun aworan, Getty Images Lowolowo bayii, milionu mokanlelogbon ni won ti wa ninu ebi ogaja-fowo-meke, gege bi esi abajade iwadii ajo FAO se so.. | yo | bbc |
Orisun aworan, NGFMAFS Omowe Abubukar Suleiman ni igbakeji aare tele fun ajo FAO lorileede Naijiria, o si salaye ona marun-un to nilo lati gba. | yo | bbc |
Orisun aworan, Getty Images Lowolowo bayii, milionu mokanlelogbon ni won ti wa ninu ebi ogaja-fowo-meke, gege bi esi abajade iwadii ajo FAO se so. | yo | bbc |
Awon mokanlelogorin eeyan ni won ti wa ni bebe lati ma se ri ounje je mo ni odun mefa si asiko yii, gege bi ajo naa tun se ko o jade.. | yo | bbc |
Omowe Abubukar Suleiman ni igbakeji aare tele fun ajo FAO lorileede Naijiria, o si salaye ona marun-un to nilo lati gba. | yo | bbc |
Orisun aworan, Getty Images Lowolowo bayii, milionu mokanlelogbon ni won ti wa ninu ebi ogaja-fowo-meke, gege bi esi abajade iwadii ajo FAO se so. | yo | bbc |
Awon mokanlelogorin eeyan ni won ti wa ni bebe lati ma se ri ounje je mo ni odun mefa si asiko yii, gege bi ajo naa tun se ko o jade. | yo | bbc |
"Ohun kan gboogi to si fa ohun to n sele yii ni eto oro aje ile Naijiria," Omowe Suleiman lo so bee. | yo | bbc |
"Bi owo ounje ati awon nnkan lilo miran se n lo soke ti se iranwo gidi.". | yo | bbc |
Orisun aworan, Getty Images Lowolowo bayii, milionu mokanlelogbon ni won ti wa ninu ebi ogaja-fowo-meke, gege bi esi abajade iwadii ajo FAO se so. | yo | bbc |
Awon mokanlelogorin eeyan ni won ti wa ni bebe lati ma se ri ounje je mo ni odun mefa si asiko yii, gege bi ajo naa tun se ko o jade. | yo | bbc |
"Ohun kan gboogi to si fa ohun to n sele yii ni eto oro aje ile Naijiria," Omowe Suleiman lo so bee. | yo | bbc |
"Bi owo ounje ati awon nnkan lilo miran se n lo soke ti se iranwo gidi." O fi kun un pe alekun lori owo epo bentiroolu lo fa a ti owo awon oja fi lo soke, to si n nira lati ra, nitori pe gbogbo ire oko patapata ni won n gbe gba ori ile.. | yo | bbc |
Lowolowo bayii, milionu mokanlelogbon ni won ti wa ninu ebi ogaja-fowo-meke, gege bi esi abajade iwadii ajo FAO se so. | yo | bbc |
Awon mokanlelogorin eeyan ni won ti wa ni bebe lati ma se ri ounje je mo ni odun mefa si asiko yii, gege bi ajo naa tun se ko o jade. | yo | bbc |
"Ohun kan gboogi to si fa ohun to n sele yii ni eto oro aje ile Naijiria," Omowe Suleiman lo so bee. | yo | bbc |
"Bi owo ounje ati awon nnkan lilo miran se n lo soke ti se iranwo gidi." O fi kun un pe alekun lori owo epo bentiroolu lo fa a ti owo awon oja fi lo soke, to si n nira lati ra, nitori pe gbogbo ire oko patapata ni won n gbe gba ori ile. | yo | bbc |
"Wahala eto aabo naa tun je ki awon eeyan sa, to si n je ki won padanu awon oko won.". | yo | bbc |
Awon mokanlelogorin eeyan ni won ti wa ni bebe lati ma se ri ounje je mo ni odun mefa si asiko yii, gege bi ajo naa tun se ko o jade. | yo | bbc |
"Ohun kan gboogi to si fa ohun to n sele yii ni eto oro aje ile Naijiria," Omowe Suleiman lo so bee. | yo | bbc |
"Bi owo ounje ati awon nnkan lilo miran se n lo soke ti se iranwo gidi." O fi kun un pe alekun lori owo epo bentiroolu lo fa a ti owo awon oja fi lo soke, to si n nira lati ra, nitori pe gbogbo ire oko patapata ni won n gbe gba ori ile. | yo | bbc |
"Wahala eto aabo naa tun je ki awon eeyan sa, to si n je ki won padanu awon oko won." Orisun aworan, Sulaiman Abubakar. | yo | bbc |
"Ohun kan gboogi to si fa ohun to n sele yii ni eto oro aje ile Naijiria," Omowe Suleiman lo so bee. | yo | bbc |
"Bi owo ounje ati awon nnkan lilo miran se n lo soke ti se iranwo gidi." O fi kun un pe alekun lori owo epo bentiroolu lo fa a ti owo awon oja fi lo soke, to si n nira lati ra, nitori pe gbogbo ire oko patapata ni won n gbe gba ori ile. | yo | bbc |
"Wahala eto aabo naa tun je ki awon eeyan sa, to si n je ki won padanu awon oko won." Orisun aworan, Sulaiman Abubakar Omowe Abubukar Suleiman so pe awon igbese kiakia ati eyi ti yoo je olojo pipe wa lati gbe. | yo | bbc |
O fi kun un pe alekun lori owo epo bentiroolu lo fa a ti owo awon oja fi lo soke, to si n nira lati ra, nitori pe gbogbo ire oko patapata ni won n gbe gba ori ile. | yo | bbc |
"Wahala eto aabo naa tun je ki awon eeyan sa, to si n je ki won padanu awon oko won." Orisun aworan, Sulaiman Abubakar Omowe Abubukar Suleiman so pe awon igbese kiakia ati eyi ti yoo je olojo pipe wa lati gbe. | yo | bbc |
O salaye re lekunrere bayii: Akosemose naa so pe awon eeyan kan wa ti won ti bori ni ti won, to si ni awon wonyi ni ajo WFP fi si ipo keji ati ipo keta ninu ipele ebi.. | yo | bbc |
"Wahala eto aabo naa tun je ki awon eeyan sa, to si n je ki won padanu awon oko won." Orisun aworan, Sulaiman Abubakar Omowe Abubukar Suleiman so pe awon igbese kiakia ati eyi ti yoo je olojo pipe wa lati gbe. | yo | bbc |
O salaye re lekunrere bayii: Akosemose naa so pe awon eeyan kan wa ti won ti bori ni ti won, to si ni awon wonyi ni ajo WFP fi si ipo keji ati ipo keta ninu ipele ebi. | yo | bbc |
O ni awon eeyan yii nilo ki won ran won lowo nitori pe ko siye ohun ti won le se lati ri ounje nitori pe won ko ni ona lati mo bi won yoo se rii.. | yo | bbc |
Orisun aworan, Sulaiman Abubakar Omowe Abubukar Suleiman so pe awon igbese kiakia ati eyi ti yoo je olojo pipe wa lati gbe. | yo | bbc |
End of preview. Expand
in Dataset Viewer.
README.md exists but content is empty.
Use the Edit dataset card button to edit it.
- Downloads last month
- 40