text
stringlengths 44
22.5k
| language
stringclasses 1
value | source
stringclasses 2
values |
---|---|---|
O salaye re lekunrere bayii: Akosemose naa so pe awon eeyan kan wa ti won ti bori ni ti won, to si ni awon wonyi ni ajo WFP fi si ipo keji ati ipo keta ninu ipele ebi. | yo | bbc |
O ni awon eeyan yii nilo ki won ran won lowo nitori pe ko siye ohun ti won le se lati ri ounje nitori pe won ko ni ona lati mo bi won yoo se rii. | yo | bbc |
Awon eeyan ko fi bee da oko mo, bee si ni won ko kowo le ori ise agbe ati ogbin mo nitori wahala ati isoro eto aabo.. | yo | bbc |
Omowe Abubukar Suleiman so pe awon igbese kiakia ati eyi ti yoo je olojo pipe wa lati gbe. | yo | bbc |
O salaye re lekunrere bayii: Akosemose naa so pe awon eeyan kan wa ti won ti bori ni ti won, to si ni awon wonyi ni ajo WFP fi si ipo keji ati ipo keta ninu ipele ebi. | yo | bbc |
O ni awon eeyan yii nilo ki won ran won lowo nitori pe ko siye ohun ti won le se lati ri ounje nitori pe won ko ni ona lati mo bi won yoo se rii. | yo | bbc |
Awon eeyan ko fi bee da oko mo, bee si ni won ko kowo le ori ise agbe ati ogbin mo nitori wahala ati isoro eto aabo. | yo | bbc |
Awon eeyan n da oko sugbon won ko ri ere nibe, nitori pe awon ologun ti ko gbogbo ire ati anfaani won lo, tabi ka so pe won nilo lati san owo ori.. | yo | bbc |
Akosemose naa so pe awon eeyan kan wa ti won ti bori ni ti won, to si ni awon wonyi ni ajo WFP fi si ipo keji ati ipo keta ninu ipele ebi. | yo | bbc |
O ni awon eeyan yii nilo ki won ran won lowo nitori pe ko siye ohun ti won le se lati ri ounje nitori pe won ko ni ona lati mo bi won yoo se rii. | yo | bbc |
Awon eeyan ko fi bee da oko mo, bee si ni won ko kowo le ori ise agbe ati ogbin mo nitori wahala ati isoro eto aabo. | yo | bbc |
Awon eeyan n da oko sugbon won ko ri ere nibe, nitori pe awon ologun ti ko gbogbo ire ati anfaani won lo, tabi ka so pe won nilo lati san owo ori. | yo | bbc |
Awon nnkan wonyi maa n fa ki ounje po lati se jade.. | yo | bbc |
O ni awon eeyan yii nilo ki won ran won lowo nitori pe ko siye ohun ti won le se lati ri ounje nitori pe won ko ni ona lati mo bi won yoo se rii. | yo | bbc |
Awon eeyan ko fi bee da oko mo, bee si ni won ko kowo le ori ise agbe ati ogbin mo nitori wahala ati isoro eto aabo. | yo | bbc |
Awon eeyan n da oko sugbon won ko ri ere nibe, nitori pe awon ologun ti ko gbogbo ire ati anfaani won lo, tabi ka so pe won nilo lati san owo ori. | yo | bbc |
O pon dandan lati mu ayipada ba ona ti a n gba lati da oko, paapaa julo awon oko ti a n da sori ogbe ile ati bi a se n toju awon ire oko, ki awon ounje ma ba a baje nibi ti a ba toju won si.. | yo | bbc |
Awon eeyan ko fi bee da oko mo, bee si ni won ko kowo le ori ise agbe ati ogbin mo nitori wahala ati isoro eto aabo. | yo | bbc |
Awon eeyan n da oko sugbon won ko ri ere nibe, nitori pe awon ologun ti ko gbogbo ire ati anfaani won lo, tabi ka so pe won nilo lati san owo ori. | yo | bbc |
O pon dandan lati mu ayipada ba ona ti a n gba lati da oko, paapaa julo awon oko ti a n da sori ogbe ile ati bi a se n toju awon ire oko, ki awon ounje ma ba a baje nibi ti a ba toju won si. | yo | bbc |
Awon eso igbalode la nilo lati maa se, ti ko won ko si ni nilo opo omi.. | yo | bbc |
Awon eeyan n da oko sugbon won ko ri ere nibe, nitori pe awon ologun ti ko gbogbo ire ati anfaani won lo, tabi ka so pe won nilo lati san owo ori. | yo | bbc |
O pon dandan lati mu ayipada ba ona ti a n gba lati da oko, paapaa julo awon oko ti a n da sori ogbe ile ati bi a se n toju awon ire oko, ki awon ounje ma ba a baje nibi ti a ba toju won si. | yo | bbc |
Awon eso igbalode la nilo lati maa se, ti ko won ko si ni nilo opo omi. | yo | bbc |
Ijoba nilo lati se iranwo fawon agbe keekeeke nitori pe awon ni igi leyin ogba fun ise agbe ni Naijiria.. | yo | bbc |
O pon dandan lati mu ayipada ba ona ti a n gba lati da oko, paapaa julo awon oko ti a n da sori ogbe ile ati bi a se n toju awon ire oko, ki awon ounje ma ba a baje nibi ti a ba toju won si. | yo | bbc |
Awon eso igbalode la nilo lati maa se, ti ko won ko si ni nilo opo omi. | yo | bbc |
Ijoba nilo lati se iranwo fawon agbe keekeeke nitori pe awon ni igi leyin ogba fun ise agbe ni Naijiria. | yo | bbc |
Kii se pe ijo pe ijoba ko pese iranwo, wahala to wa nibe ni pe ko de odo awon agbe to wa lorileede. | yo | bbc |

BBC ko mo nipa awon ohun ti o wa ni awon oju opo ti o wa ni ita. | yo | bbc |

Orisun aworan, x/Bola Ahmed Tinubu/agriculture nigeria Kii se iroyin tuntun mo pe Aare Bola Ahmed Tinubu ti orileede Naijiria ti da eka ileese ijoba ti yoo maa ri soro awon nnkan osin, eyi ti won n pe ni 'Livestock' sile. | yo | bbc |
Lara awon ojuse ti ileese yii yoo maa bojuto ni bi alaafia ati ilera pipe yoo se tubo wa fun awon ohun osin, paapaa julo lati pana aawo to n sele laarin awon darandaran ati awon agbe nile Naijiria. | yo | bbc |
Opo igba ti ko lo n ka ni aawo ti be sile laarin awon darandaran, paapaa awon Fulani darandaran ati agbe, to si ti mu emi dani nipa fifi eran jeko. | yo | bbc |
Idasile ileese yii ni ijoba apapo nigbagbo pe yoo fi opin si gbogbo wahala ati idunkooko naa.. | yo | bbc |
Kii se iroyin tuntun mo pe Aare Bola Ahmed Tinubu ti orileede Naijiria ti da eka ileese ijoba ti yoo maa ri soro awon nnkan osin, eyi ti won n pe ni 'Livestock' sile. | yo | bbc |
Lara awon ojuse ti ileese yii yoo maa bojuto ni bi alaafia ati ilera pipe yoo se tubo wa fun awon ohun osin, paapaa julo lati pana aawo to n sele laarin awon darandaran ati awon agbe nile Naijiria. | yo | bbc |
Opo igba ti ko lo n ka ni aawo ti be sile laarin awon darandaran, paapaa awon Fulani darandaran ati agbe, to si ti mu emi dani nipa fifi eran jeko. | yo | bbc |
Idasile ileese yii ni ijoba apapo nigbagbo pe yoo fi opin si gbogbo wahala ati idunkooko naa. | yo | bbc |
Latigba ti ijoba apapo ti kede idasile eka ileese yii ni orisirisi awuyewuye ti n lo kaakiri igboro. | yo | bbc |
Bi awon kan se n so pe igbese to dara ni, bee lawon miran n so pe ohun to kan ko leyi.. | yo | bbc |
Lara awon ojuse ti ileese yii yoo maa bojuto ni bi alaafia ati ilera pipe yoo se tubo wa fun awon ohun osin, paapaa julo lati pana aawo to n sele laarin awon darandaran ati awon agbe nile Naijiria. | yo | bbc |
Opo igba ti ko lo n ka ni aawo ti be sile laarin awon darandaran, paapaa awon Fulani darandaran ati agbe, to si ti mu emi dani nipa fifi eran jeko. | yo | bbc |
Idasile ileese yii ni ijoba apapo nigbagbo pe yoo fi opin si gbogbo wahala ati idunkooko naa. | yo | bbc |
Latigba ti ijoba apapo ti kede idasile eka ileese yii ni orisirisi awuyewuye ti n lo kaakiri igboro. | yo | bbc |
Bi awon kan se n so pe igbese to dara ni, bee lawon miran n so pe ohun to kan ko leyi. | yo | bbc |
Sibe, BBC YORUBA ti wa kan si awon ojogbon ati awon onimo ijinle nipa ise agbe ati ogbin, paapaa nipa ohun osin nile Afrika lati soro, onikaluku won si so erongba won.. | yo | bbc |
Opo igba ti ko lo n ka ni aawo ti be sile laarin awon darandaran, paapaa awon Fulani darandaran ati agbe, to si ti mu emi dani nipa fifi eran jeko. | yo | bbc |
Idasile ileese yii ni ijoba apapo nigbagbo pe yoo fi opin si gbogbo wahala ati idunkooko naa. | yo | bbc |
Latigba ti ijoba apapo ti kede idasile eka ileese yii ni orisirisi awuyewuye ti n lo kaakiri igboro. | yo | bbc |
Bi awon kan se n so pe igbese to dara ni, bee lawon miran n so pe ohun to kan ko leyi. | yo | bbc |
Sibe, BBC YORUBA ti wa kan si awon ojogbon ati awon onimo ijinle nipa ise agbe ati ogbin, paapaa nipa ohun osin nile Afrika lati soro, onikaluku won si so erongba won. | yo | bbc |
Won ni igbese to dara ni ijoba gbe, ati pe yoo mu idagbasoke ba eto ise agbe ati ogbin, to fi mo ohun osin.. | yo | bbc |
Idasile ileese yii ni ijoba apapo nigbagbo pe yoo fi opin si gbogbo wahala ati idunkooko naa. | yo | bbc |
Latigba ti ijoba apapo ti kede idasile eka ileese yii ni orisirisi awuyewuye ti n lo kaakiri igboro. | yo | bbc |
Bi awon kan se n so pe igbese to dara ni, bee lawon miran n so pe ohun to kan ko leyi. | yo | bbc |
Sibe, BBC YORUBA ti wa kan si awon ojogbon ati awon onimo ijinle nipa ise agbe ati ogbin, paapaa nipa ohun osin nile Afrika lati soro, onikaluku won si so erongba won. | yo | bbc |
Won ni igbese to dara ni ijoba gbe, ati pe yoo mu idagbasoke ba eto ise agbe ati ogbin, to fi mo ohun osin. | yo | bbc |
Omowe Samson Adeola Odedina to je ogbontarigi nidi ise agbe ati ogbin lorileede Naijiria nigba to n salaye fun BBC YORUBA laipe yii, o ni igbese to dara ni ijoba apapo gbe lati mu idagbasoke ba eka naa.. | yo | bbc |
Latigba ti ijoba apapo ti kede idasile eka ileese yii ni orisirisi awuyewuye ti n lo kaakiri igboro. | yo | bbc |
Bi awon kan se n so pe igbese to dara ni, bee lawon miran n so pe ohun to kan ko leyi. | yo | bbc |
Sibe, BBC YORUBA ti wa kan si awon ojogbon ati awon onimo ijinle nipa ise agbe ati ogbin, paapaa nipa ohun osin nile Afrika lati soro, onikaluku won si so erongba won. | yo | bbc |
Won ni igbese to dara ni ijoba gbe, ati pe yoo mu idagbasoke ba eto ise agbe ati ogbin, to fi mo ohun osin. | yo | bbc |
Omowe Samson Adeola Odedina to je ogbontarigi nidi ise agbe ati ogbin lorileede Naijiria nigba to n salaye fun BBC YORUBA laipe yii, o ni igbese to dara ni ijoba apapo gbe lati mu idagbasoke ba eka naa. | yo | bbc |
Omowe Odedina to je komisanna ana foro eto ise agbe ati ogbin nipinle Ogun so pe ise agbe pin sorisirisi eka, gege bi ise dokita naa se pin sorisirisi eka.. | yo | bbc |
Sibe, BBC YORUBA ti wa kan si awon ojogbon ati awon onimo ijinle nipa ise agbe ati ogbin, paapaa nipa ohun osin nile Afrika lati soro, onikaluku won si so erongba won. | yo | bbc |
Won ni igbese to dara ni ijoba gbe, ati pe yoo mu idagbasoke ba eto ise agbe ati ogbin, to fi mo ohun osin. | yo | bbc |
Omowe Samson Adeola Odedina to je ogbontarigi nidi ise agbe ati ogbin lorileede Naijiria nigba to n salaye fun BBC YORUBA laipe yii, o ni igbese to dara ni ijoba apapo gbe lati mu idagbasoke ba eka naa. | yo | bbc |
Omowe Odedina to je komisanna ana foro eto ise agbe ati ogbin nipinle Ogun so pe ise agbe pin sorisirisi eka, gege bi ise dokita naa se pin sorisirisi eka. | yo | bbc |
"Ti e ba wo o, ise agbe gbooro gidi, bi ise dokita naa ni. | yo | bbc |
Nidi ise dokita, e maa sakiyesi pe awon dokita to n wo oju wa, awon ti imu wa loto, awon to n se ese naa wa loto, ati beebeelo. | yo | bbc |

"A ti fi oju tembelu ise agbe ni a ko se mo pe bo se se pataki to niyen, nitori pe ohun nikan la le se lai gba iwe ase nidi e.. | yo | bbc |
Omowe Samson Adeola Odedina to je ogbontarigi nidi ise agbe ati ogbin lorileede Naijiria nigba to n salaye fun BBC YORUBA laipe yii, o ni igbese to dara ni ijoba apapo gbe lati mu idagbasoke ba eka naa. | yo | bbc |
Omowe Odedina to je komisanna ana foro eto ise agbe ati ogbin nipinle Ogun so pe ise agbe pin sorisirisi eka, gege bi ise dokita naa se pin sorisirisi eka. | yo | bbc |
"Ti e ba wo o, ise agbe gbooro gidi, bi ise dokita naa ni. | yo | bbc |
Nidi ise dokita, e maa sakiyesi pe awon dokita to n wo oju wa, awon ti imu wa loto, awon to n se ese naa wa loto, ati beebeelo. | yo | bbc |
"A ti fi oju tembelu ise agbe ni a ko se mo pe bo se se pataki to niyen, nitori pe ohun nikan la le se lai gba iwe ase nidi e. | yo | bbc |
Ni ise agbe yii, ohun ti elomiran gbajumo ni oro adie; elomiran wa to je pe tolotolo, awon miran gbajumo eran ati awon nnkan miran bee.. | yo | bbc |