audio
audioduration (s) 1.5
28.1
| sentence
stringlengths 2
128
| normalised_sentence
stringlengths 2
128
| wer
float64 0
5
| generated_sentence
stringlengths 2
326
|
---|---|---|---|---|
ààntéré dé odò òrìṣàomi ri ọmọ rẹ o fi iji nla fa ààntéré wọ inú omi lai padà | aantere de odo orisaomi ri omo re o fi iji nla fa aantere wo inu omi lai pada | 0.333333 | Antere de odo Orisa omi ri omo re, o fi iji nla fa antere wo inu omi lai pada. |
|
kò tán | ko tan | 1 | Ko tan. |
|
àwọn ti ó ni àwọn kò fẹ lọ si iléiwé bẹrẹ si pa ọmọ àwọn ti ó fẹ lọ | awon ti o ni awon ko fe lo si ileiwe bere si pa omo awon ti o fe lo | 0.157895 | awon ti o ni awon o fe lo si ile iwe bere si pa omo awon ti o fe lo |
|
kíló nṣẹlẹ yorùbá ni àgbà kì wá lọjà ki orí ọmọ tuntun wọ | kilo nsele yoruba ni agba ki wa loja ki ori omo tuntun wo | 0.692308 | Ki lo n sele Yoruba ni agbaki wa loja ki ori omo tuntun n wo? |
|
sọ aya ọmọ rẹ di orogún | so aya omo re di orogun | 0.5 | So ara omo re di orogun. |
|
òjó dàda àìná táíwò kẹhinde ati bebe lo je orúkọ amu tọrun wa | ojo dada aina taiwo kehinde ati bebe lo je oruko amu torun wa | 0.692308 | Ojo, dada, aina, taewo, kehinde, ati beebee lo je oruko amuntanhun wa. |
|
ilẹ aláwọ dúdú kún fún wàrà àti oyin nítorí ọgọrundinmarun ohun àlùmọnì gbogbo àgbáyé wà ni orílẹ èdè naa | ile alawo dudu kun fun wara ati oyin nitori ogorundinmarun ohun alumoni gbogbo agbaye wa ni orile ede naa | 0.368421 | Ile alawo dudu kun fun wara ati oyin, nitori ogorun-un din marun-un ohun alumooni gbogbo agbaye wa ni orile ede naa. |
|
ní ọjọ ẹti ọjọ keji lelogun oṣu keji ọdún yi ẹrọ amóhùn máwòrán iluọba tu asiri ọmọkùnrin kan ti o | ni ojo eti ojo keji lelogun osu keji odun yi ero amohun maworan iluoba tu asiri omokunrin kan ti o | 0.4 | Ni ojo eti ojo keji le logun osu keji odun yii, ero amohunmaworan ilu oba tu asiri omokunrin kan ti o. |
|
ewédú dùn pẹlú gbẹgìrì tàbi ọbẹ ata lati fi jẹ ẹkọ àmàlà láfún àti ounjẹ òkèlè yókù bi ẹbà iyán | ewedu dun pelu gbegiri tabi obe ata lati fi je eko amala lafun ati ounje okele yoku bi eba iyan | 0.2 | Ewe dudu pelu gbegiri tabi obe ata lati fi je eko amala lafun ati ounje okele yooku bi eba yan. |
|
tani ẹni tí ó ni fìlà tí kò lórí | tani eni ti o ni fila ti ko lori | 0.222222 | Tani eni ti o ni fila ti ko lori. |
|
iṣẹ ibi ti ó ṣe ni igbà ayé rẹ fihan pé o ni ikù ló mọ ikà | ise ibi ti o se ni igba aye re fihan pe o ni iku lo mo ika | 0.117647 | ise ibi ti o se ni igba aye re fihan pe oni iku lo mo ika |
|
èrè awọn ìwà ìbàjẹ wọnyi ti ba ìlú jẹ èyi jẹ ikan ninu ohun ti ó dá kún ohun ti | ere awon iwa ibaje wonyi ti ba ilu je eyi je ikan ninu ohun ti o da kun ohun ti | 0.55 | Ere ati iwa ibaje wonyi ti ba ilu je, eyi je eyi ti adanikanjopon aladari. |
|
ni asiko ọdún pàtàkì asiko ọdún iranti ọjọ ibi jésù bi oúnjẹ ti pọ tó fún ọpọlọpọ ti o wa | ni asiko odun pataki asiko odun iranti ojo ibi jesu bi ounje ti po to fun opolopo ti o wa | 0.2 | Ni asiko odun pataki, asiko odun iranti ojo ibi Jesu bi ounje ti po to fun opolopo ti o wa. |
|
ikeji fún ọpọlọpọ idi | ikeji fun opolopo idi | 0.5 | Ikeji fun opolopo idi. |
|
bí a ti nṣe ní ilé wa ewọ ibòmíì | bi a ti nse ni ile wa ewo ibomii | 0.666667 | Bi a ti n se ni ile wa, ewo ibo mi. |
|
ẹ fojú sọnà fún àwọn ọja yókù | e foju sona fun awon oja yoku | 0.571429 | E fojusona fun awon oja yooku. |
|
ọkùnrin àti obìnrin mọ lọjọ òní ni ọjọ kan yorùbá orílẹ èdè nàíjíríà àti gbogbo ilẹ aláwọ dúdú yio ṣe | okunrin ati obinrin mo lojo oni ni ojo kan yoruba orile ede naijiria ati gbogbo ile alawo dudu yio se | 0.05 | okunrin ati obinrin mo lojo oni ni ojo kan yoruba orile ede nigeria ati gbogbo ile alawo dudu yio se |
|
ayé irú ẹni bẹẹ | aye iru eni bee | 0.75 | Aye iu eni bee. |
|
ìwà oriṣiriṣi ni ó ma ńhàn ni ilé olórogún àrùn ìyàwó ti ó ńjalè purọ ṣe àgbèrè aláisàn ti ó | iwa orisirisi ni o ma nhan ni ile olorogun arun iyawo ti o njale puro se agbere alaisan ti o | 0.35 | iwa orisiwisi ni o ma n han ni ile olorogun arun iyawo ti o n jale buru o se agbere alaisan ti o |
|
kọjá | koja | 1 | Koja. |
|
bi a bá fi òwe yi ṣe akiyesi aṣọ àlòkù ti wọn kó wọ ìlú npa ọrọ ilẹ wa | bi a ba fi owe yi se akiyesi aso aloku ti won ko wo ilu npa oro ile wa | 0.368421 | Bi a ba fi owe yii se akiyesi, aso alopo ti won ko wo ilu n pa oro ile wa. |
|
ọpọlọpọ aṣọ àgbàwọ yi kò wà fún ara àti lilò ni ilẹ aláwọdúdú | opolopo aso agbawo yi ko wa fun ara ati lilo ni ile alawodudu | 0.615385 | Opolopo aso agba wo yii ko wa fun ara ati ilu. |
|
oúnje ọlọra ti iyọja tàbí tí iyọ ìrèké pọ nínú rẹ | ounje olora ti iyoja tabi ti iyo ireke po ninu re | 0.454545 | Ounje olora ti iyo ja tabi ti iyo ereke po ninu re. |
|
nibi ti wọn ti ńja ògì ti o jẹ ounjẹ àárọ àwọn ọmọ bàbá beyioṣe dànù | nibi ti won ti nja ogi ti o je ounje aaro awon omo baba beyiose danu | 0.3125 | nibi ti won ti n jaogi ti o je ounje aaro awon omo baba be yio se danu |
|
rò wípé aṣírí fẹ tú á gbé ìwé sílẹ pé òhun kò ṣe mọ nítorí ki ipò òhun má ba | ro wipe asiri fe tu a gbe iwe sile pe ohun ko se mo nitori ki ipo ohun ma ba | 0.15 | ro wipe asiri fe tu a gbe iwe sile pe oun ko se mo nitori ki ipo oun ma baa |
|
ẹlòmíràn kò ni ṣe iwadi ohun ti àwọn èniyàn fi ńsáré ki ó tó bẹrẹ si sáré | elomiran ko ni se iwadi ohun ti awon eniyan fi nsare ki o to bere si sare | 0.411765 | Elomiran ko ni se iwadii ohun awon eniyan fi n sare ki o to bere si n sare. |
|
jẹ ẹ rántí áwọn ti ko ri | je e ranti awon ti ko ri | 0.571429 | Je eran ti awon ti ko ri. |
|
yorùbá ni òriṣà òkè jẹ ki npé méjì obinrin kò dé nú | yoruba ni orisa oke je ki npe meji obinrin ko de nu | 0.333333 | yoruba ni orisa oke je ki n pe meji obinrin ko denu |
|
kò sí àyè fún ọmọ irú àwọn bayi lati mọ wọn lójú nítorí wọn o si nílé lati ṣe ojuṣe | ko si aye fun omo iru awon bayi lati mo won loju nitori won o si nile lati se ojuse | 0.35 | Ko si aaye fun omo iru awon bayii lati mo won loju nitorin wo ohun si nile lati se ojuse. |
|
ọba olóyè ọlọrọ àti aláìní ilẹ yorùbá ló fẹràn àti rán ọmọ wọn lọ si iléiwé bi àwọn fúnra wọn | oba oloye oloro ati alaini ile yoruba lo feran ati ran omo won lo si ileiwe bi awon funra won | 0.15 | oba oloye oloro ati alaini ile yuropa lo feran ati ran omo won lo si ile iwe bi awon funra won |
|
nígbàtí bàbá ti gbìyànjú titi ti kò mọ ohun ti ó tún lè ṣe mọ lati tẹ aiyé lọrùn ni | nigbati baba ti gbiyanju titi ti ko mo ohun ti o tun le se mo lati te aiye lorun ni | 0.1 | nigbati baba ti gbiyanju titi ti ko mo ohun ti o tun le se mo lati te aye lohun ni |
|
ariwo sọ ṣùgbọn ìtìjú bo àjàpá | ariwo so sugbon itiju bo ajapa | 0.666667 | Ariwo so, sugbon itiju bo aja pa. |
|
àwọn enia ti o ri wọn ni bàbá iwọ gun kẹtẹkẹtẹ ọmọ ńrin ni ilẹ | awon enia ti o ri won ni baba iwo gun ketekete omo nrin ni ile | 0.333333 | awon eniyan ti o ri won ni baba iwogun ketekete omo n rin ni ile |
|
nígbàtí ọjọ ti àjàpá dá pé ẹlẹdẹ reti titi ki ó wá san owó ti ó yá ṣùgbọn àjàpá kò | nigbati ojo ti ajapa da pe elede reti titi ki o wa san owo ti o ya sugbon ajapa ko | 0 | nigbati ojo ti ajapa da pe elede reti titi ki o wa san owo ti o ya sugbon ajapa ko |
|
mọ | mo | 1 | Mo |
|
níwọntúnwọnsìn | niwontunwonsin | 4 | niwon tun won se |
|
àti bẹẹbẹ lọ | ati beebe lo | 1.333333 | Ati bee bee lo. |
|
àrùn ara tinumi aya aṣojúọba bẹrẹ si han nítorí ó sọ ìyàwó ọmọ rẹ di orogún | arun ara tinumi aya asojuoba bere si han nitori o so iyawo omo re di orogun | 0.25 | arun ara tinu mi aya asoju oba bere si han nitori o so iyawo omo re di orogun |
|
nítorí ìfẹ owó ti ó gbòde láyé òde òní mu | nitori ife owo ti o gbode laye ode oni mu | 0.3 | Nitori ife owo ti o gbode laye ode oniimu |
|
iwe ìrìnà | iwe irina | 1 | Iwe irinna. |
|
ọrọ yorùbá sọ wípé ọwọ ọmọde ko to pẹpẹ tagbalagba ko wọ kèrègbè èyí tí a lè túmọ sí wípé | oro yoruba so wipe owo omode ko to pepe tagbalagba ko wo keregbe eyi ti a le tumo si wipe | 0.15 | oro Yoruba so wipe owo omode ko to pepe tagbalagba ko wo kere gbe eyi ti a le tumo si wipe |
|
bi wọn dé ipò giga wọn ki fẹ kúrò wọn a paniyan wọn a jalè wọn a ta enia wọn | bi won de ipo giga won ki fe kuro won a paniyan won a jale won a ta enia won | 0.4 | Bi won de ipo giga, won ki i fe kuro, won a paniyan, won a jale, won a ta eniyan won. |
|
àjàpá wá ronú ọgbọn ti ó lè dá lati pèsè àkàrà fún òhun àti idilé rẹ | ajapa wa ronu ogbon ti o le da lati pese akara fun ohun ati idile re | 0 | ajapa wa ronu ogbon ti o le da lati pese akara fun ohun ati idile re |
|
èdè wọn | ede won | 1 | Ede won. |
|
kọ láti kọ ẹkọ tàbi kó kọ iṣẹ ọwọ | ko lati ko eko tabi ko ko ise owo | 0.222222 | Ko lati ko eko tabi ko ko ise owo. |
|
nkankan lọ ti ayé bá parẹ nitotọ | nkankan lo ti aye ba pare nitoto | 0.285714 | Nnkankan lo ti aye ba pare nitooto. |
|
kò si iná omi iléìwé fún ọmọ aláìní ojú ọnà ti bàjẹ awọn ará ilú njẹ ìyà ọpọlọpọ ọdọ jade | ko si ina omi ileiwe fun omo alaini oju ona ti baje awon ara ilu nje iya opolopo odo jade | 0.5 | Ko si ina, omi, ile-iwe fun omo alaini, oju ona ti baje, awon ara ilu n je iya, opolopo odo jade. |
|
àṣepọ laarin ará ìlúọba àti yorùbá ti lè ni ọgọrun ọdún nítorí eyi kò si ibi ti enia dé ni | asepo laarin ara iluoba ati yoruba ti le ni ogorun odun nitori eyi ko si ibi ti enia de ni | 0.2 | asepo laarin ara ilu oba ati yuropi ti le ni ogorun odun nitori eyi ko si ibi ti eniyan de ni |
|
òwe yi bá àwọn ti ó ṣe jura wọn lọ tàbi ki ó jẹ igbèsè lati ra ẹbùn oúnjẹ ti | owe yi ba awon ti o se jura won lo tabi ki o je igbese lati ra ebun ounje ti | 0.1 | owe yii ba awon ti o n se jura won lo tabi ki o je igbese lati ra ebun ounje ti |
|
títí dé òkèòkun | titi de okeokun | 1 | Titi de oke okun. |
|
ẹbí ìyàwó le sọ wípé ki ẹgbẹ wọ aṣọ aláwọ ewé lati ba ohun yọ ayọ ìgbéyàwó ki ẹbí ọkọ | ebi iyawo le so wipe ki egbe wo aso alawo ewe lati ba ohun yo ayo igbeyawo ki ebi oko | 0.45 | ebi iyawo le so wipe ki egbewo aso alawo iwe lati ba ohun yoo yo |
|
yorùbá ni ọmọdé ò jobì àgbà ò jẹ oye òwe yi bá àwọn òbí ti ó kọ ọmọ sílẹ ìyá | yoruba ni omode o jobi agba o je oye owe yi ba awon obi ti o ko omo sile iya | 0.2 | Yoruba ni omode ojobi agba o je oye owe yi ba awon obi ti o ko omo sile iya. |
|
olóyè yorùbá ti ó bá fi ipò tàbi ọlá hu iwà ikà ni ayé igbàlódé yi kò ri ibi pamọ | oloye yoruba ti o ba fi ipo tabi ola hu iwa ika ni aye igbalode yi ko ri ibi pamo | 0.1 | oloye yoruba ti o ba fi ipo tabi ola wu iwa ika ni aye igbalode yii ko ri ibi pamo |
|
àwọn obinrin mẹta yi o ṣeni laanu wípé kò rí ọjọ ayọ ìtúsílẹ nínú ìdè tí ariel castro fi àwọn | awon obinrin meta yi o seni laanu wipe ko ri ojo ayo itusile ninu ide ti ariel castro fi awon | 0.1 | awon obinrin meta yi o seni laanu wipe ko ri ojo ayo itusile ninu ide ti ere kastro fi awon |
|
kò si ìyàtọ laarin ìjọba ológun àti òṣèlú | ko si iyato laarin ijoba ologun ati oselu | 0.375 | Ko si iyato laaarin ijoba ologun ati oselu. |
|
bi eré bi àwàdà dákúdájí iná mọnàmọná bẹrẹ ni àsikò ìjọba sagari ni bi ọdún mẹtàlélọgbọn sẹhin | bi ere bi awada dakudaji ina monamona bere ni asiko ijoba sagari ni bi odun metalelogbon sehin | 0.411765 | Bi ere bi awada, daku daji ina monamona bere ni asiko ijoba sagare ni bi i odun metalelogbon seyin. |
|
pé ọmọ ohun kò ni fẹ àyànfẹ | pe omo ohun ko ni fe ayanfe | 0.428571 | Pe omo oun ko ni fe ayanfe. |
|
àwọn ológun ti yin ọkànlélógún sókè lati ki ọmọ titun káàbọ si ayé | awon ologun ti yin okanlelogun soke lati ki omo titun kaabo si aye | 0.615385 | awon ologun ti yin okanlelogun tun |
|
èkó ò ní bàjẹ o | eko o ni baje o | 0.6 | Ekoo ni baje o. |
|
nígbàtí wèrè ko ti wọ àṣà aṣọ ẹbí ẹnití o ṣe ìyàwó ṣe òkú sọ ọmọ lórúkọ àti ṣiṣe yoku | nigbati were ko ti wo asa aso ebi eniti o se iyawo se oku so omo loruko ati sise yoku | 0.45 | Nigba ti were ko ti wo asa aso ebi, eni ti o se iyawo, se oku, so omo oloruko ati sise yooku. |
|
yorùbá ma nlo àwọn àròsọ itàn wọnyi lati kọ àwọn ọmọdé ni ẹkọ | yoruba ma nlo awon aroso itan wonyi lati ko awon omode ni eko | 0.153846 | yoruba ma n lo awon aroso itan wonyi lati ko awon omode ni eko |
|
láyé òde òní ọmọdé le gbójúlé àgbàlagbà ṣùgbọn ọpọlọpọ àgbàlagbà gbójúlé ọmọdé láti kọ lílò ẹrọ ayélujára | laye ode oni omode le gbojule agbalagba sugbon opolopo agbalagba gbojule omode lati ko lilo ero ayelujara | 0.235294 | Laye ode oni, omode le gbojule agbalagba, sugbon opolopo agbalagba gbojule omode lati ko lilo ero ayelujara. |
|
ni ọjọ ìsọmọ lórúkọ tàbi ìkómọ bàbá ìyá ẹbi àti ọrẹ òbí ọmọ tuntun á fi ìdùnnú hàn nípa ṣíṣe | ni ojo isomo loruko tabi ikomo baba iya ebi ati ore obi omo tuntun a fi idunnu han nipa sise | 0 | ni ojo isomo loruko tabi ikomo baba iya ebi ati ore obi omo tuntun a fi idunnu han nipa sise |
|
ohun pẹlú ọmọ ti ó ti bi tẹlẹ ni wọn gbé jù si ẹwọn fún ẹsùn pé kò yẹ ki | ohun pelu omo ti o ti bi tele ni won gbe ju si ewon fun esun pe ko ye ki | 0.1 | ohun pelu omo ti o ti bi tele ni won gbeju si ewon fun esun pe ko ye ki |
|
iroyin awọn ọdọ òṣìṣẹ ti o nṣi kúrò ni ilẹ aláwọ dúdú ti ọkọ wọn dà si òkun ni ìlú | iroyin awon odo osise ti o nsi kuro ni ile alawo dudu ti oko won da si okun ni ilu | 0.15 | iroyin awon odo osise ti o n si n kuro ni ile alawo dudu ti oko won da si okun ni ilu |
|
ìwà burúkú kò mọ àgbà tàbí àwọ nítorí náà o yẹ ka kíyèsára pàtàkì àwọn òbí | iwa buruku ko mo agba tabi awo nitori naa o ye ka kiyesara pataki awon obi | 0.6875 | Iwa buruku ko mo agba tabi awo. |
|
ariwo yi pọ to bẹ gẹ ti àtisùn di ogun | ariwo yi po to be ge ti atisun di ogun | 0.7 | Ariwo yii po to bege ti a ti sun di ogun. |
|
àwọn òṣèlú tó yẹ ki wọn gbé èdè ìlú wọn lárugẹ n dá kún pí pa èdè rẹ | awon oselu to ye ki won gbe ede ilu won laruge n da kun pi pa ede re | 0.166667 | Awon oselu to ye ki won gbe ede ilu won laruge n da kun pipa ede re |
|
ṣi wúlò fún àwọn ọmọdé tí ó lè ṣe àṣàyàn lati fi etí si àgbà kọ ẹkọ tàbí ka àkọsílẹ | si wulo fun awon omode ti o le se asayan lati fi eti si agba ko eko tabi ka akosile | 0.1 | si wulo fun awon omode ti o le se aso yan lati fi eti si agba ko eko tabi ka akosile |
|
gómnà ẹ kú orire adọọta ọjọ ìbí orire naa dalẹ ẹmí ọlá á gùn lati ṣe ọpọlọpọ ọjọ ìbí láyé | gomna e ku orire adoota ojo ibi orire naa dale emi ola a gun lati se opolopo ojo ibi laye | 0.45 | Gomina eku orire aadota ojo ibi. Orire naa dale emi ola aagun lati se opolopo ojo ibi laye. |
|
òfin | ofin | 1 | Ofin. |
|
erin jẹ ẹranko ti ọlọrun da lọlá pẹlu titobi rẹ ninu igbo | erin je eranko ti olorun da lola pelu titobi re ninu igbo | 0.25 | Erin je eranko ti Olorun da lola pelu titobi re ninu igbo. |
|
òwe yorùbá ti ó ni ṣòkòtò àgbàwọ bi kò ṣoni lẹsẹ á fúnni nítan | owe yoruba ti o ni sokoto agbawo bi ko soni lese a funni nitan | 0.5 | Owe Yoruba ti o ni sokoto agba wo bi ko soni lese afonini nitan. |
|
ninú ìtàn bi àjàpá ti sọ ẹlẹdẹ di ọbùn ti a mọ si titi di oni àjàpá jẹ ẹranko ti | ninu itan bi ajapa ti so elede di obun ti a mo si titi di oni ajapa je eranko ti | 0.7 | Ninu itan bi ajapa ti so elede bi obun. |
|
bẹẹ | bee | 0 | bee |
|
àwọn ẹyà wọnyi ni èkó – ti olú ilú rẹ jẹ ìkẹjà èkiti – ti olú ilú rẹ jẹ adóèkiti | awon eya wonyi ni eko – ti olu ilu re je ikeja ekiti – ti olu ilu re je adoekiti | 0.2 | awon eya wonyi ni eko ti olu ilu re je ikeja ekiti ti olu ilu re je ado ekiti |
|
ara rẹ ẹni tó mbinu mbinu ara rẹ nítorí ẹni tó kú ti lọ | ara re eni to mbinu mbinu ara re nitori eni to ku ti lo | 0.5 | Ara re, eni to n binu n binu ara re nitori eni to ku ti lo. |
|
wọn sowọ pọ lati tú orílẹ èdè ṣe ni pàtàkì ìpèsè ohun amáyédẹrùn | won sowo po lati tu orile ede se ni pataki ipese ohun amayederun | 0.153846 | won n sowopo lati tu orile ede se ni pataki ipese ohun amayederun |
|
ọlá ninú orúkọ yorùbá ki ṣe owó àti ohun ini nikan yorùbá ka ilera si ọlà | ola ninu oruko yoruba ki se owo ati ohun ini nikan yoruba ka ilera si ola | 0.125 | ola ninu ofuruko yoruba ki i se owo ati ohun ini nikan yoruba ka ilera si ola |
|
kò si ohun ti àjàpá lè ṣe lai ni idi tàbi ọgbọn àrékérekè nítorí eyi ó sọ ara rẹ di | ko si ohun ti ajapa le se lai ni idi tabi ogbon arekereke nitori eyi o so ara re di | 0.1 | ko si ohun ti ajapa le se laini idi tabi ogbon arekereke nitori eyi o so ara re di |
|
lẹhin ìgbéyàwó lati fi han wípé wọn ti di ara kan | lehin igbeyawo lati fi han wipe won ti di ara kan | 0.363636 | Leyin igbeyawo lati fihan wipe won ti di ara kan. |
|
àjàpá dìde ó wá fọhùn wípé gbogbo àlébù ti gbogbo wọn sọ nípa ìyàwó wọn kéré lára ti ìyàwó ohun | ajapa dide o wa fohun wipe gbogbo alebu ti gbogbo won so nipa iyawo won kere lara ti iyawo ohun | 0.1 | ajapa dide o wa fun un wipe gbogbo alebu ti gbogbo won so nipa iyawo won kere lara ti iyawo ohun |
|
ọdọ miran a wọ asọ àti bàtà òtútù ninu ooru | odo miran a wo aso ati bata otutu ninu ooru | 0.3 | Odo miiran, a wo aso ati bata otutu ninu ooru. |
|
a le lo òwe yi lati kilọ fun ẹni to fẹ lọ si òkèòkun lọna kọna lai ni ase tabi | a le lo owe yi lati kilo fun eni to fe lo si okeokun lona kona lai ni ase tabi | 0.25 | a le lo owe yi lati kilo fun eni to fe lo si oke okun lonakona laini ase tabi |
|
èrò ilú kò ni dibò fún irú ẹni bẹẹ | ero ilu ko ni dibo fun iru eni bee | 0.222222 | Ero ilu ko ni dibo fun iru eni bee. |
|
ori igbe ògì ti ó dànù ni àwọn ọmọ wa nígbàtí bàbá beyioṣe wọlé | ori igbe ogi ti o danu ni awon omo wa nigbati baba beyiose wole | 0.285714 | ori igbeogi ti o danu ni awon omo wa nigbati baba beyo se wole |
|
ọmọ to yi ko gbọn ìyá ni ko ma ṣa kú kilo npa ọmọ bi agọ yẹwò | omo to yi ko gbon iya ni ko ma sa ku kilo npa omo bi ago yewo | 0.352941 | omo to yi ko gbon iya ni ko ma saku ki lo n pa omo bii ago yewo |
|
gbogbo olólùfẹ èdè yorùbá pàtàkì àwọn ti o fi ìfẹ tẹ lé àkọsílẹ ọrọ gbígbé èdè àti àṣà yorùbá | gbogbo ololufe ede yoruba pataki awon ti o fi ife te le akosile oro gbigbe ede ati asa yoruba | 0.578947 | gbogbo ololufe ede yuropa pataki awon ti o fe ife |
|
títí di bi ọgbọn ọdún sẹhin àti rí oúnjẹ yorùbá rà ṣọwọn | titi di bi ogbon odun sehin ati ri ounje yoruba ra sowon | 0.583333 | Titi di bi ogbon odun seyin, a ti re ounje Yoruba ra sowon. |
|
àwọn àlejò tí a pè sí ibi ìyàwó lati ṣe iṣẹ ibi | awon alejo ti a pe si ibi iyawo lati se ise ibi | 0.166667 | Awon alejo ti a pe si ibi iyawo lati se ise ibi. |
|
ni gbogbo àsìkò ti adarí ìwé fi wa ni ilé ìṣòro nla ni lati lè kọ ìwé lori ayélujára nítorí | ni gbogbo asiko ti adari iwe fi wa ni ile isoro nla ni lati le ko iwe lori ayelujara nitori | 0.05 | ni gbogbo asiko ti adari iwe fi wa ni ile isoro nla ni lati ko iwe lori ayelujara nitori |
|
àmọtékùn fi eré si ṣùgbọn gbogbo ọṣẹ ti ó wà ninu kànrìnkàn ti ta àbàwọn si ara rẹ lati ori | amotekun fi ere si sugbon gbogbo ose ti o wa ninu kanrinkan ti ta abawon si ara re lati ori | 0.1 | amotekun fi ere si sugbon gbogbo ose ti o wa ninu karin kan ti ta abawon si ara re lati ori |
|
ti a ba ṣakiyesi ọpọ ọmọ to dagba si èkó ko mọ wipe yorùbá ni ju ọbẹ ata ati ẹfọ | ti a ba sakiyesi opo omo to dagba si eko ko mo wipe yoruba ni ju obe ata ati efo | 0.3 | Ti a ba sakiyesi opo omo to dagba si Eko ko mo wipe Yoruba ni ju obe ati ata eko. |
|
àti ọmọdé àti àgbà ló fẹrán àkàrà | ati omode ati agba lo feran akara | 0.285714 | Ati omode ati agba lo feran akara. |
|
ki lọ | ki lo | 1 | Kii lo? |
|
wọn tú jáde lati fi ọpọ dibò àti bójú tó ibò wọn lati gbé góminà ọgbẹni rauf arẹgbẹṣọlá padà | won tu jade lati fi opo dibo ati boju to ibo won lati gbe gomina ogbeni rauf aregbesola pada | 0.105263 | won tun jade lati fi opo dibo ati boju to ibo won lati gbe gomina ogbeni raouf aregbesola pada |
|
pàtàkì ni igba ọgbẹlẹ nígbàtí iṣẹ oko din kù | pataki ni igba ogbele nigbati ise oko din ku | 0.777778 | Pataki nigba ogbele nigba ti ise oko dinku. |
|
yorùbá ni ohun tó yẹ ni lo yẹ ni òkùnkùn o yẹ ọmọ eniyan nítorí òkùnkùn ti iléiṣẹ mọnàmọná fa | yoruba ni ohun to ye ni lo ye ni okunkun o ye omo eniyan nitori okunkun ti ileise monamona fa | 0.3 | Yoruba ni, ohun to ye ni lo ye ni, okunkun o ye omo eniyan nitori okunkun ti ile ise monamona fa a. |
|
wọn gba ìdájọ èyí ti wọn ni lati lo ọgbọn ọdún ó kéré jù | won gba idajo eyi ti won ni lati lo ogbon odun o kere ju | 0.214286 | Won gba idajo eyi ti won ni lati lo ogbon odun wo kere ju. |
|
yorùbá lọkùnrin ati lobirin ẹ ranti wipe odò to ba gbagbe orisun rẹ gbigbe lo ma ngbe | yoruba lokunrin ati lobirin e ranti wipe odo to ba gbagbe orisun re gbigbe lo ma ngbe | 0.352941 | Yoruba lokunrin ati lobinrin, e ranti wipe odo to ba gbagbe orisun re, gbigbe lo mo n gbe. |
End of preview. Expand
in Dataset Viewer.
README.md exists but content is empty.
Use the Edit dataset card button to edit it.
- Downloads last month
- 35