audio
audioduration (s) 1.5
28.1
| sentence
stringlengths 2
128
| normalised_sentence
stringlengths 2
128
|
---|---|---|
ààntéré dé odò òrìṣàomi ri ọmọ rẹ o fi iji nla fa ààntéré wọ inú omi lai padà | aantere de odo orisaomi ri omo re o fi iji nla fa aantere wo inu omi lai pada |
|
kò tán | ko tan |
|
àwọn ti ó ni àwọn kò fẹ lọ si iléiwé bẹrẹ si pa ọmọ àwọn ti ó fẹ lọ | awon ti o ni awon ko fe lo si ileiwe bere si pa omo awon ti o fe lo |
|
kíló nṣẹlẹ yorùbá ni àgbà kì wá lọjà ki orí ọmọ tuntun wọ | kilo nsele yoruba ni agba ki wa loja ki ori omo tuntun wo |
|
sọ aya ọmọ rẹ di orogún | so aya omo re di orogun |
|
òjó dàda àìná táíwò kẹhinde ati bebe lo je orúkọ amu tọrun wa | ojo dada aina taiwo kehinde ati bebe lo je oruko amu torun wa |
|
ilẹ aláwọ dúdú kún fún wàrà àti oyin nítorí ọgọrundinmarun ohun àlùmọnì gbogbo àgbáyé wà ni orílẹ èdè naa | ile alawo dudu kun fun wara ati oyin nitori ogorundinmarun ohun alumoni gbogbo agbaye wa ni orile ede naa |
|
ní ọjọ ẹti ọjọ keji lelogun oṣu keji ọdún yi ẹrọ amóhùn máwòrán iluọba tu asiri ọmọkùnrin kan ti o | ni ojo eti ojo keji lelogun osu keji odun yi ero amohun maworan iluoba tu asiri omokunrin kan ti o |
|
ewédú dùn pẹlú gbẹgìrì tàbi ọbẹ ata lati fi jẹ ẹkọ àmàlà láfún àti ounjẹ òkèlè yókù bi ẹbà iyán | ewedu dun pelu gbegiri tabi obe ata lati fi je eko amala lafun ati ounje okele yoku bi eba iyan |
|
tani ẹni tí ó ni fìlà tí kò lórí | tani eni ti o ni fila ti ko lori |
|
iṣẹ ibi ti ó ṣe ni igbà ayé rẹ fihan pé o ni ikù ló mọ ikà | ise ibi ti o se ni igba aye re fihan pe o ni iku lo mo ika |
|
èrè awọn ìwà ìbàjẹ wọnyi ti ba ìlú jẹ èyi jẹ ikan ninu ohun ti ó dá kún ohun ti | ere awon iwa ibaje wonyi ti ba ilu je eyi je ikan ninu ohun ti o da kun ohun ti |
|
ni asiko ọdún pàtàkì asiko ọdún iranti ọjọ ibi jésù bi oúnjẹ ti pọ tó fún ọpọlọpọ ti o wa | ni asiko odun pataki asiko odun iranti ojo ibi jesu bi ounje ti po to fun opolopo ti o wa |
|
ikeji fún ọpọlọpọ idi | ikeji fun opolopo idi |
|
bí a ti nṣe ní ilé wa ewọ ibòmíì | bi a ti nse ni ile wa ewo ibomii |
|
ẹ fojú sọnà fún àwọn ọja yókù | e foju sona fun awon oja yoku |
|
ọkùnrin àti obìnrin mọ lọjọ òní ni ọjọ kan yorùbá orílẹ èdè nàíjíríà àti gbogbo ilẹ aláwọ dúdú yio ṣe | okunrin ati obinrin mo lojo oni ni ojo kan yoruba orile ede naijiria ati gbogbo ile alawo dudu yio se |
|
ayé irú ẹni bẹẹ | aye iru eni bee |
|
ìwà oriṣiriṣi ni ó ma ńhàn ni ilé olórogún àrùn ìyàwó ti ó ńjalè purọ ṣe àgbèrè aláisàn ti ó | iwa orisirisi ni o ma nhan ni ile olorogun arun iyawo ti o njale puro se agbere alaisan ti o |
|
kọjá | koja |
|
bi a bá fi òwe yi ṣe akiyesi aṣọ àlòkù ti wọn kó wọ ìlú npa ọrọ ilẹ wa | bi a ba fi owe yi se akiyesi aso aloku ti won ko wo ilu npa oro ile wa |
|
ọpọlọpọ aṣọ àgbàwọ yi kò wà fún ara àti lilò ni ilẹ aláwọdúdú | opolopo aso agbawo yi ko wa fun ara ati lilo ni ile alawodudu |
|
oúnje ọlọra ti iyọja tàbí tí iyọ ìrèké pọ nínú rẹ | ounje olora ti iyoja tabi ti iyo ireke po ninu re |
|
nibi ti wọn ti ńja ògì ti o jẹ ounjẹ àárọ àwọn ọmọ bàbá beyioṣe dànù | nibi ti won ti nja ogi ti o je ounje aaro awon omo baba beyiose danu |
|
rò wípé aṣírí fẹ tú á gbé ìwé sílẹ pé òhun kò ṣe mọ nítorí ki ipò òhun má ba | ro wipe asiri fe tu a gbe iwe sile pe ohun ko se mo nitori ki ipo ohun ma ba |
|
ẹlòmíràn kò ni ṣe iwadi ohun ti àwọn èniyàn fi ńsáré ki ó tó bẹrẹ si sáré | elomiran ko ni se iwadi ohun ti awon eniyan fi nsare ki o to bere si sare |
|
jẹ ẹ rántí áwọn ti ko ri | je e ranti awon ti ko ri |
|
yorùbá ni òriṣà òkè jẹ ki npé méjì obinrin kò dé nú | yoruba ni orisa oke je ki npe meji obinrin ko de nu |
|
kò sí àyè fún ọmọ irú àwọn bayi lati mọ wọn lójú nítorí wọn o si nílé lati ṣe ojuṣe | ko si aye fun omo iru awon bayi lati mo won loju nitori won o si nile lati se ojuse |
|
ọba olóyè ọlọrọ àti aláìní ilẹ yorùbá ló fẹràn àti rán ọmọ wọn lọ si iléiwé bi àwọn fúnra wọn | oba oloye oloro ati alaini ile yoruba lo feran ati ran omo won lo si ileiwe bi awon funra won |
|
nígbàtí bàbá ti gbìyànjú titi ti kò mọ ohun ti ó tún lè ṣe mọ lati tẹ aiyé lọrùn ni | nigbati baba ti gbiyanju titi ti ko mo ohun ti o tun le se mo lati te aiye lorun ni |
|
ariwo sọ ṣùgbọn ìtìjú bo àjàpá | ariwo so sugbon itiju bo ajapa |
|
àwọn enia ti o ri wọn ni bàbá iwọ gun kẹtẹkẹtẹ ọmọ ńrin ni ilẹ | awon enia ti o ri won ni baba iwo gun ketekete omo nrin ni ile |
|
nígbàtí ọjọ ti àjàpá dá pé ẹlẹdẹ reti titi ki ó wá san owó ti ó yá ṣùgbọn àjàpá kò | nigbati ojo ti ajapa da pe elede reti titi ki o wa san owo ti o ya sugbon ajapa ko |
|
mọ | mo |
|
níwọntúnwọnsìn | niwontunwonsin |
|
àti bẹẹbẹ lọ | ati beebe lo |
|
àrùn ara tinumi aya aṣojúọba bẹrẹ si han nítorí ó sọ ìyàwó ọmọ rẹ di orogún | arun ara tinumi aya asojuoba bere si han nitori o so iyawo omo re di orogun |
|
nítorí ìfẹ owó ti ó gbòde láyé òde òní mu | nitori ife owo ti o gbode laye ode oni mu |
|
iwe ìrìnà | iwe irina |
|
ọrọ yorùbá sọ wípé ọwọ ọmọde ko to pẹpẹ tagbalagba ko wọ kèrègbè èyí tí a lè túmọ sí wípé | oro yoruba so wipe owo omode ko to pepe tagbalagba ko wo keregbe eyi ti a le tumo si wipe |
|
bi wọn dé ipò giga wọn ki fẹ kúrò wọn a paniyan wọn a jalè wọn a ta enia wọn | bi won de ipo giga won ki fe kuro won a paniyan won a jale won a ta enia won |
|
àjàpá wá ronú ọgbọn ti ó lè dá lati pèsè àkàrà fún òhun àti idilé rẹ | ajapa wa ronu ogbon ti o le da lati pese akara fun ohun ati idile re |
|
èdè wọn | ede won |
|
kọ láti kọ ẹkọ tàbi kó kọ iṣẹ ọwọ | ko lati ko eko tabi ko ko ise owo |
|
nkankan lọ ti ayé bá parẹ nitotọ | nkankan lo ti aye ba pare nitoto |
|
kò si iná omi iléìwé fún ọmọ aláìní ojú ọnà ti bàjẹ awọn ará ilú njẹ ìyà ọpọlọpọ ọdọ jade | ko si ina omi ileiwe fun omo alaini oju ona ti baje awon ara ilu nje iya opolopo odo jade |
|
àṣepọ laarin ará ìlúọba àti yorùbá ti lè ni ọgọrun ọdún nítorí eyi kò si ibi ti enia dé ni | asepo laarin ara iluoba ati yoruba ti le ni ogorun odun nitori eyi ko si ibi ti enia de ni |
|
òwe yi bá àwọn ti ó ṣe jura wọn lọ tàbi ki ó jẹ igbèsè lati ra ẹbùn oúnjẹ ti | owe yi ba awon ti o se jura won lo tabi ki o je igbese lati ra ebun ounje ti |
|
títí dé òkèòkun | titi de okeokun |
|
ẹbí ìyàwó le sọ wípé ki ẹgbẹ wọ aṣọ aláwọ ewé lati ba ohun yọ ayọ ìgbéyàwó ki ẹbí ọkọ | ebi iyawo le so wipe ki egbe wo aso alawo ewe lati ba ohun yo ayo igbeyawo ki ebi oko |
|
yorùbá ni ọmọdé ò jobì àgbà ò jẹ oye òwe yi bá àwọn òbí ti ó kọ ọmọ sílẹ ìyá | yoruba ni omode o jobi agba o je oye owe yi ba awon obi ti o ko omo sile iya |
|
olóyè yorùbá ti ó bá fi ipò tàbi ọlá hu iwà ikà ni ayé igbàlódé yi kò ri ibi pamọ | oloye yoruba ti o ba fi ipo tabi ola hu iwa ika ni aye igbalode yi ko ri ibi pamo |
|
àwọn obinrin mẹta yi o ṣeni laanu wípé kò rí ọjọ ayọ ìtúsílẹ nínú ìdè tí ariel castro fi àwọn | awon obinrin meta yi o seni laanu wipe ko ri ojo ayo itusile ninu ide ti ariel castro fi awon |
|
kò si ìyàtọ laarin ìjọba ológun àti òṣèlú | ko si iyato laarin ijoba ologun ati oselu |
|
bi eré bi àwàdà dákúdájí iná mọnàmọná bẹrẹ ni àsikò ìjọba sagari ni bi ọdún mẹtàlélọgbọn sẹhin | bi ere bi awada dakudaji ina monamona bere ni asiko ijoba sagari ni bi odun metalelogbon sehin |
|
pé ọmọ ohun kò ni fẹ àyànfẹ | pe omo ohun ko ni fe ayanfe |
|
àwọn ológun ti yin ọkànlélógún sókè lati ki ọmọ titun káàbọ si ayé | awon ologun ti yin okanlelogun soke lati ki omo titun kaabo si aye |
|
èkó ò ní bàjẹ o | eko o ni baje o |
|
nígbàtí wèrè ko ti wọ àṣà aṣọ ẹbí ẹnití o ṣe ìyàwó ṣe òkú sọ ọmọ lórúkọ àti ṣiṣe yoku | nigbati were ko ti wo asa aso ebi eniti o se iyawo se oku so omo loruko ati sise yoku |
|
yorùbá ma nlo àwọn àròsọ itàn wọnyi lati kọ àwọn ọmọdé ni ẹkọ | yoruba ma nlo awon aroso itan wonyi lati ko awon omode ni eko |
|
láyé òde òní ọmọdé le gbójúlé àgbàlagbà ṣùgbọn ọpọlọpọ àgbàlagbà gbójúlé ọmọdé láti kọ lílò ẹrọ ayélujára | laye ode oni omode le gbojule agbalagba sugbon opolopo agbalagba gbojule omode lati ko lilo ero ayelujara |
|
ni ọjọ ìsọmọ lórúkọ tàbi ìkómọ bàbá ìyá ẹbi àti ọrẹ òbí ọmọ tuntun á fi ìdùnnú hàn nípa ṣíṣe | ni ojo isomo loruko tabi ikomo baba iya ebi ati ore obi omo tuntun a fi idunnu han nipa sise |
|
ohun pẹlú ọmọ ti ó ti bi tẹlẹ ni wọn gbé jù si ẹwọn fún ẹsùn pé kò yẹ ki | ohun pelu omo ti o ti bi tele ni won gbe ju si ewon fun esun pe ko ye ki |
|
iroyin awọn ọdọ òṣìṣẹ ti o nṣi kúrò ni ilẹ aláwọ dúdú ti ọkọ wọn dà si òkun ni ìlú | iroyin awon odo osise ti o nsi kuro ni ile alawo dudu ti oko won da si okun ni ilu |
|
ìwà burúkú kò mọ àgbà tàbí àwọ nítorí náà o yẹ ka kíyèsára pàtàkì àwọn òbí | iwa buruku ko mo agba tabi awo nitori naa o ye ka kiyesara pataki awon obi |
|
ariwo yi pọ to bẹ gẹ ti àtisùn di ogun | ariwo yi po to be ge ti atisun di ogun |
|
àwọn òṣèlú tó yẹ ki wọn gbé èdè ìlú wọn lárugẹ n dá kún pí pa èdè rẹ | awon oselu to ye ki won gbe ede ilu won laruge n da kun pi pa ede re |
|
ṣi wúlò fún àwọn ọmọdé tí ó lè ṣe àṣàyàn lati fi etí si àgbà kọ ẹkọ tàbí ka àkọsílẹ | si wulo fun awon omode ti o le se asayan lati fi eti si agba ko eko tabi ka akosile |
|
gómnà ẹ kú orire adọọta ọjọ ìbí orire naa dalẹ ẹmí ọlá á gùn lati ṣe ọpọlọpọ ọjọ ìbí láyé | gomna e ku orire adoota ojo ibi orire naa dale emi ola a gun lati se opolopo ojo ibi laye |
|
òfin | ofin |
|
erin jẹ ẹranko ti ọlọrun da lọlá pẹlu titobi rẹ ninu igbo | erin je eranko ti olorun da lola pelu titobi re ninu igbo |
|
òwe yorùbá ti ó ni ṣòkòtò àgbàwọ bi kò ṣoni lẹsẹ á fúnni nítan | owe yoruba ti o ni sokoto agbawo bi ko soni lese a funni nitan |
|
ninú ìtàn bi àjàpá ti sọ ẹlẹdẹ di ọbùn ti a mọ si titi di oni àjàpá jẹ ẹranko ti | ninu itan bi ajapa ti so elede di obun ti a mo si titi di oni ajapa je eranko ti |
|
bẹẹ | bee |
|
àwọn ẹyà wọnyi ni èkó – ti olú ilú rẹ jẹ ìkẹjà èkiti – ti olú ilú rẹ jẹ adóèkiti | awon eya wonyi ni eko – ti olu ilu re je ikeja ekiti – ti olu ilu re je adoekiti |
|
ara rẹ ẹni tó mbinu mbinu ara rẹ nítorí ẹni tó kú ti lọ | ara re eni to mbinu mbinu ara re nitori eni to ku ti lo |
|
wọn sowọ pọ lati tú orílẹ èdè ṣe ni pàtàkì ìpèsè ohun amáyédẹrùn | won sowo po lati tu orile ede se ni pataki ipese ohun amayederun |
|
ọlá ninú orúkọ yorùbá ki ṣe owó àti ohun ini nikan yorùbá ka ilera si ọlà | ola ninu oruko yoruba ki se owo ati ohun ini nikan yoruba ka ilera si ola |
|
kò si ohun ti àjàpá lè ṣe lai ni idi tàbi ọgbọn àrékérekè nítorí eyi ó sọ ara rẹ di | ko si ohun ti ajapa le se lai ni idi tabi ogbon arekereke nitori eyi o so ara re di |
|
lẹhin ìgbéyàwó lati fi han wípé wọn ti di ara kan | lehin igbeyawo lati fi han wipe won ti di ara kan |
|
àjàpá dìde ó wá fọhùn wípé gbogbo àlébù ti gbogbo wọn sọ nípa ìyàwó wọn kéré lára ti ìyàwó ohun | ajapa dide o wa fohun wipe gbogbo alebu ti gbogbo won so nipa iyawo won kere lara ti iyawo ohun |
|
ọdọ miran a wọ asọ àti bàtà òtútù ninu ooru | odo miran a wo aso ati bata otutu ninu ooru |
|
a le lo òwe yi lati kilọ fun ẹni to fẹ lọ si òkèòkun lọna kọna lai ni ase tabi | a le lo owe yi lati kilo fun eni to fe lo si okeokun lona kona lai ni ase tabi |
|
èrò ilú kò ni dibò fún irú ẹni bẹẹ | ero ilu ko ni dibo fun iru eni bee |
|
ori igbe ògì ti ó dànù ni àwọn ọmọ wa nígbàtí bàbá beyioṣe wọlé | ori igbe ogi ti o danu ni awon omo wa nigbati baba beyiose wole |
|
ọmọ to yi ko gbọn ìyá ni ko ma ṣa kú kilo npa ọmọ bi agọ yẹwò | omo to yi ko gbon iya ni ko ma sa ku kilo npa omo bi ago yewo |
|
gbogbo olólùfẹ èdè yorùbá pàtàkì àwọn ti o fi ìfẹ tẹ lé àkọsílẹ ọrọ gbígbé èdè àti àṣà yorùbá | gbogbo ololufe ede yoruba pataki awon ti o fi ife te le akosile oro gbigbe ede ati asa yoruba |
|
títí di bi ọgbọn ọdún sẹhin àti rí oúnjẹ yorùbá rà ṣọwọn | titi di bi ogbon odun sehin ati ri ounje yoruba ra sowon |
|
àwọn àlejò tí a pè sí ibi ìyàwó lati ṣe iṣẹ ibi | awon alejo ti a pe si ibi iyawo lati se ise ibi |
|
ni gbogbo àsìkò ti adarí ìwé fi wa ni ilé ìṣòro nla ni lati lè kọ ìwé lori ayélujára nítorí | ni gbogbo asiko ti adari iwe fi wa ni ile isoro nla ni lati le ko iwe lori ayelujara nitori |
|
àmọtékùn fi eré si ṣùgbọn gbogbo ọṣẹ ti ó wà ninu kànrìnkàn ti ta àbàwọn si ara rẹ lati ori | amotekun fi ere si sugbon gbogbo ose ti o wa ninu kanrinkan ti ta abawon si ara re lati ori |
|
ti a ba ṣakiyesi ọpọ ọmọ to dagba si èkó ko mọ wipe yorùbá ni ju ọbẹ ata ati ẹfọ | ti a ba sakiyesi opo omo to dagba si eko ko mo wipe yoruba ni ju obe ata ati efo |
|
àti ọmọdé àti àgbà ló fẹrán àkàrà | ati omode ati agba lo feran akara |
|
ki lọ | ki lo |
|
wọn tú jáde lati fi ọpọ dibò àti bójú tó ibò wọn lati gbé góminà ọgbẹni rauf arẹgbẹṣọlá padà | won tu jade lati fi opo dibo ati boju to ibo won lati gbe gomina ogbeni rauf aregbesola pada |
|
pàtàkì ni igba ọgbẹlẹ nígbàtí iṣẹ oko din kù | pataki ni igba ogbele nigbati ise oko din ku |
|
yorùbá ni ohun tó yẹ ni lo yẹ ni òkùnkùn o yẹ ọmọ eniyan nítorí òkùnkùn ti iléiṣẹ mọnàmọná fa | yoruba ni ohun to ye ni lo ye ni okunkun o ye omo eniyan nitori okunkun ti ileise monamona fa |
|
wọn gba ìdájọ èyí ti wọn ni lati lo ọgbọn ọdún ó kéré jù | won gba idajo eyi ti won ni lati lo ogbon odun o kere ju |
|
yorùbá lọkùnrin ati lobirin ẹ ranti wipe odò to ba gbagbe orisun rẹ gbigbe lo ma ngbe | yoruba lokunrin ati lobirin e ranti wipe odo to ba gbagbe orisun re gbigbe lo ma ngbe |
End of preview. Expand
in Dataset Viewer.
README.md exists but content is empty.
Use the Edit dataset card button to edit it.
- Downloads last month
- 46