audio
audioduration (s)
1.19
51.8
sentence
stringlengths
12
391
Lọ fá irun rẹ kó tó wù.
Ìbọn ló bàá l’ẹ́sẹ̀.
Ọwọ́ mi ni kẹ́ẹ wò.
Òṣogbo ni wọ́n ti gbé àgbò náà bọ̀.
Ọ̀rúnmìlà nìkan ló gbọ́ ohùn ẹnu Olódùmarè yékéyéke.
Gbénró ló pe ẹjọ́ kòtẹ́milọ́rùn.
Bí babaláwo náà ṣẹ̀ gba ibẹ̀ kọjá ni.
Ọmọ bàba olówó ni mí.
Abẹ́ igi Ọ̀dán ni wọ́n ti máa ń sábà pa ààlọ́.
Ilẹ̀kùn yàrá Tádé ti bàjẹ́.
Òǹkà Yorùbá ni mo kọ́ àwọn ènìyàn níbi ìpàdé àná.
Désọ́lá lọ wẹ̀ lódò.
Bàbá àgbà, ṣé ẹ ti jí?
Bísí jẹ́ ìyàwó kejì.
Àwọn Yorùbá kò fi ọwọ́ yẹpẹrẹ mú ọrọ ọmọ bíbí láwùjọ.
Ẹlẹ́nu bótobòto, a ó ma wírú yó ma wírù.
Mú aṣọ kúrò nílẹ̀.
Wọ́n so ẹran mọ́ ‘lẹ̀ lọ́jọ́ iléyá.
Ikú Olóògbé Dúró Ládiípọ̀ dun gbogbo ìlú.
Arómáṣọdún bímọ ọkùnrin làǹtilanti.
Òwe lẹ ó máa pa, ẹ ò ní pànìyàn.
Àpò ṣaka ni wọ́n kó gbogbo ẹrù wọn sí nígbà tí wọ́n lọ sí ìrìn àjò náà.
Ẹranko ti Jíbádé fẹ́ràn jù ni akọ ajá.
Kí a máa dán ìgbàgbọ́ wa wò.
Wọ́n mú ọmọ náà ṣeré.
Àwàdà ni a fi bẹ̀rẹ̀ ọ̀rọ̀ náà.
Ẹnikẹ́ni tí ìwọ́ bá ní ipá láti ṣe ìrànlọ́wọ́ fún òun ni ẹnìkejì re.
Láfún ni a jẹ.
Mo ra ìwé mẹ́ta níbẹ̀.
Ìsọkúsọ Àmọ́dù ti pọ̀ jù.
Kí ló dé tò ń pè mí lánàá?
Orí àdògán ni wọ́n ti ń rokà.
Òòrùn ò tíì wọ̀ tán.
Kí ló dé tí àwọn kan ma ń bínú tí wọ́n bá̀ ṣàpèjúwe wọn gẹ́gẹ́ bí i è̀nìyàn sísanra?
Mo ní’fẹ̀ẹ́ bí o ṣe máa ń rẹ́rìn-ín.
Mo fẹ́ ra ẹyin bíbọ̀.
Ilé epo náà tóbi, ẹ̀bá ọ̀nà ló wà.
Owó ni kókó o.
Ojúbọ òrìṣà ni owó náà wà.
Àdúrà gbogbo òbí ni kí ọmọ wọ́n ṣ’oríire.
Ra ọtí tàbí ẹmu fún wa.
Yòrùbá bọ̀ wọ́n ní, “Kò sí bí a ó ṣe se ebòlò tí kò ní rungbẹ́.”
Kò ye ká máa sọ̀rọ̀ ṣàkàṣàkà torí a ò mọ ẹni tó lè ranni lọ́wọ́.
Kò rí oorun sùn lálẹ́ àná; èyí múu bínú.
Ọ̀gọ̀njọ́ òru ni àwọn eléyi tún pariwo.
Ó ti jẹ gbèsè púpọ̀.
Mọ fẹ́ràn ẹlẹ́dẹ̀.
Ó ti sá lọ, ọ̀rọ̀ náà kọjá ohun tí agbára rẹ̀ ká.
Àdùkẹ́ ti sanra ju ọjọ́ orí rẹ̀ lọ.
Mi ò nífẹ̀ẹ́ sí àti máa jẹ ìgbá, mo nífẹ ọsàn dípò rẹ̀.
Ṣe o ti rí ìdí tí kò fi lè tètè ní ọ̀rẹ́kùnrin.
Ṣé wàá jẹ́ bàbá àwọn ọmọ mi?
Orí ẹní ni mo sùn mọ́jú.
Màá máa wá wò yìn nílé láìpẹ́.
Ọ̀la ni ìsimi ọlọ́jọ́ gbọọrọ máa bẹ̀rẹ̀.
Ọláwùnmí jẹ́ ẹni tí ó ní ìrẹ̀lẹ́.
Olórí ilé aṣòfin wà ní agbègbè náà.
Gbogbo èyí ni mo ti ṣe fún ẹ, ǹjẹ́ ìwọ́ lè ṣe èyí fún mi?
Kòkòrò ààrùn tí ò gbóògun ti pọ̀ ní ìlú yìí.
Dọ́kítà sọ pé àwọn oní gbèsè òun ò tí sanwó.
Bá mi bu omi mímu wá nínu ìkòkò tó wà l'ábàáwọlé.
Ṣé o wà ní oríi Twitter?
Bàbá àti màmá ti lọ sí òde òkú àwọn Ṣeun.
Dáre ni akọ̀wé ẹgbẹ́ akọrin inú ìjọ wa.
Kò s’ẹ́ni tó mọ Ifá tán.
A ti gé igi kan lulẹ̀.
Ìyẹn náà ni pé àwọn ìlú kékèké nínú igbó yìí náà máa ń lo iná ìjọba.
Ẹyẹlé funfun kìí bí dúdú.
Ẹranko burúkú kan ló pa àwọn ẹran náà jẹ.
Mo ò dára nínú eré bọ́ọ̀lù gbígbá.
Lọ mú àtòrì wá l’ẹ́yìn ilẹ̀kùn.
Imú ọmọ ìkókó náà dọ̀tí.
Ìsàlè àpótí ni màmá máa ń kó àwọn aṣọ olówó iyebíye wọn sí.
Ilé ìfowópamọ́ yapa nì agbègbè Adéọlá Ọdẹ́kù.
Ìdíje ńlá gbáà ni àwọn ẹgbẹ ọdẹ ń fi Ìrèmọ̀jé Ògún ṣe.
Nígbà tí ènìyàn tó burú báyì bá ń ronú kó jáwọ́ nínú ìwà ìbàjẹ́, mélòómélòó ìwọ.
Àkìtàn ọ̀hún wà níwájú.
Alágídí l’ọmọ náà, ó fi jọ ẹ̀gbọ́n rẹ̀ ni.
Èyí já sí pé, gbogbo ìmọ̀ pátá ló ń bẹ nínú ifá.
Ọ̀la ni ọdún iléyá ní Ìjẹ̀bú Òde.
Yà sí apá ọ̀tún tí o bá dé Òpópónà Ìṣẹ́ri.
Àgbàlá Bàbá Fọlákẹ́ ni àwọn ọmọ ti máa ń ṣ’eré ní ìrọ̀lẹ́.
Ṣùgbọ́n, mo já èso kan lórí igi.
Nínú gbogbo ilé ìwòsàn agbègbè yìí, ti ọ̀nà òpópónà òkìtìpupa ni ó dára díẹ̀.
Mo ti lo rí ọ̀gá mi kan lorí ọ̀rọ̀ ọ̀hún.
Àǹkárá olójúméje ni Ṣaléwá wọ̀.
Folúkẹ́ ti múra tán kí àwọn àlejòo rẹ̀ tó dé.
Ọmọ yìí ò ní àpọ́nlé kankan rárá.
Ṣé o lè yá mi l’ówó títí di ìparí oṣù.
Jọláadé kìí yẹ́ ṣerépá.
Adéògún ti d’ọjà nù.
Èròjà tí a fẹ́ fi se ọbẹ̀ kò tí ì pé o.
Ó le kú, ìjà ọ̀rẹ̀.
Ọkàn mí wúwo púpọ̀.
Ẹ jẹ́ ká sùn díẹ̀, ṣùgbọ́n oorun ò kùn mí.
Bíléèdì gé ọmọ náà ní’ka.
Mí ò ṣeré o; òdodo ọ̀rọ̀ ni.
Tí mo bá ti wà lẹ́gbẹ̀ẹ́ Ọlájùwọ́n, ara rẹ kì í lélẹ̀.
Fi ara balẹ̀ ṣá, má ṣè’jọ̀gbọ̀n.
Eéwo mú mi lábẹ́ etí.
README.md exists but content is empty. Use the Edit dataset card button to edit it.
Downloads last month
0
Edit dataset card