eng
stringlengths
1
4.84k
yor
stringlengths
1
11.4k
Appreciate your siblings ’ good qualities .
Mọyì àwọn ànímọ́ rere tí ẹ̀gbọ́n tàbí àbúrò rẹ ní .
Our Readers Ask
Àwọn Òǹkàwé Wa Béèrè Pé
Taking a stand for Bible truth is a challenge that is especially great for people who live in a non - Christian society .
Dídúró ṣinṣin fún òtítọ́ Bíbélì jẹ́ ìpèníjà ńlá , àgàgà fáwọn tó ń gbé láwùjọ tí kì í ṣe tàwọn ẹlẹ́sìn Kristẹni .
“ I became conscious of how I looked and acted , ” recalls a young man named Jared .
Ọ̀dọ́kùnrin kan tó ń jẹ́ Jared * sọ pé : “ Mo máa ń kíyè sí ìrísí mi gan - an mo sì máa ń ṣọ́ra ṣe .
According to Brazilian sleep specialist Rubens Reimão , an estimated 35 percent of the world’s population suffer from insomnia .
Gẹ́gẹ́ bí ohun tí Rubens Reimão tó jẹ́ onímọ̀ nípa oorun lórílẹ̀ - èdè Brazil sọ , àwọn ògbógi fojú bù ú pé nǹkan bí ìdá márùndínlógójì nínú ọgọ́rùn - ún àwọn èèyàn tó wà lágbàáyé ló ní ìṣòro àìróorunsùn .
Why should the cleansing of Aaron and his sons have deep meaning for all of Jehovah’s people ?
Kí nìdí tí ìwẹ̀nùmọ́ Áárónì àti ti àwọn ọmọkùnrin rẹ̀ fi yẹ kó ṣe gbogbo àwa èèyàn Jèhófà lóde òní láǹfààní ?
Rather , the disciples prayed for the courage to keep preaching .
Kàkà bẹ́ẹ̀ , ńṣe làwọn ọmọ ẹ̀yìn gbàdúrà pé káwọn lè nígboyà láti máa wàásù nìṣó .
Indeed , since they are unconscious , they cannot experience anything at all ; neither can they help or harm the living .
Torí pé wọn ò mọ nǹkan kan rárá , wọn ò ní ìmọ̀lára ohunkóhun ; wọn ò lè ran alààyè lọ́wọ́ , wọn ò sì lè fìyà jẹ wọ́n .
I dedicated my life to Jehovah and was baptized on November 20 , 1988 . ”
Mo ya ara mi sí mímọ́ fún Jèhófà , mo sì ṣe batisí ní November 20 , 1988 . ”
The malaise that afflicts the lazy person is not trifling; one-who-has-arms-that-will-not-work. Laziness is a great affliction.
Ìyà tó ńjẹ ọ̀lẹ ò kéré; a-lápá-má-ṣiṣẹ́.
In addition , committees were organized to care for those in need in the provinces of Sofala and Manica .
Láfikún sí i , wọ́n dá àwọn ìgbìmọ̀ sílẹ̀ láti bójú tó àwọn tó nílò ìrànwọ́ láwọn ẹkùn Sofala àti Manica .
However , Neugebauer and Weidner wrote in 1915 regarding the year 568 B.C.E . ( which would point to 587 B.C.E . for Jerusalem’s destruction ) that “ the moon stood 1 cubit before this star on 8 Nisan , and not on 9 Nisan . ”
Àmọ́ , Ọ̀gbẹ́ni Neugebauer àti Ọ̀gbẹ́ni Weidner kọ̀wé lọ́dún 1915 nípa ọdún 568 ṣáájú Sànmánì Kristẹni ( láti fi hàn pé ọdún 587 ṣáájú Sànmánì Kristẹni ni Jerúsálẹ́mù pa run ) pé “ Nísàn 8 ni òṣùpá dúró ní ìgbọ̀nwọ́ kan níwájú ìràwọ̀ yìí , kì í ṣe ní Nísàn 9 . ”
Eventually , it came to be an eight - hour - long photographic slide and motion picture production , complete with color and sound .
Ní àsẹ̀yìnwá àsẹ̀yìnbọ̀ , ó wá di àwòrán ara ògiri àti sinimá oníwákàtí mẹ́jọ , tó ń gbé àwọ̀ mèremère àti ohùn jáde .
How can you deal with the challenge ?
Báwo lo ṣe lè bójú tó ọ̀ràn náà ?
Other Witnesses assisted me with home chores , and eventually , local social services appointed five of them as our official home caregivers .
Wọ́n wá yan márùn - ún lára àwọn ará tó máa ń wá ràn mí lọ́wọ́ yìí gẹ́gẹ́ bí aṣojú ìjọba .
Shortly thereafter , Tessie started attending Christian meetings and displaying a Christian personality ​ — even in the face of ridicule from her associates .
Kò pẹ́ sígbà yẹn , Tessie bẹ̀rẹ̀ sí í wá sípàdé ó sì ń fi àwọn ohun tó ń kọ sílò , bó tilẹ̀ jẹ́ pé àwọn ọ̀rẹ́ rẹ̀ àtijọ́ máa ń fi í ṣe yẹ̀yẹ́ .
Get to the underlying issues .
Kí ló wà ní ìdí ọ̀rọ̀ náà ?
Paul told Titus to keep reminding Christians in Crete “ not to be belligerent , to be reasonable , exhibiting all mildness toward all men . ”
Pọ́ọ̀lù sọ fún Títù pé kó máa rán àwọn Kristẹni tó wà ní Kírétè létí “ láti má ṣe jẹ́ aríjàgbá , láti jẹ́ afòyebánilò , kí wọ́n máa fi gbogbo ìwà tútù hàn sí ènìyàn gbogbo . ”
( a ) Why might it be dangerous to follow other travelers when we are unsure about which way to go ?
( a ) Tá a bá ń rìnrìn àjò , kí nìdí tó fi léwu pé ká kàn tẹ̀ lé àwọn míì bí a kò bá mọ ibi tó yẹ ká gbà ?
For years I wondered , ‘ Why are we here , and what is the purpose of life ? ’
àti pé ‘ Kí nìdí tí Ọlọ́run tiẹ̀ fi dá wa pàápàá ? ’
This was evident when he corrected his apostles for showing a selfish , ambitious spirit . ​ — Mark 9 : 33 - 37 ; Luke 22 : 24 - 27 .
Èyí hàn nínú bó ṣe fìfẹ́ bá àwọn àpọ́sítélì rẹ̀ wí nígbà tí wọ́n ń bá ara wọn fa ọ̀rọ̀ ẹni tó tóbi jù láàárín wọn . ​ — Máàkù 9 : ​ 33 - 37 ; Lúùkù 22 : ​ 24 - 27 .
See Ephesians 5 : 17 .
Wo Éfésù 5 : 17 .
9 How You Can Cope in a Throwaway Society
9 Bó o Ṣe Lè Kẹ́sẹ Járí Nínú Ayé Alálòsọnù
SONGS TO BE USED : 201 , 132
ÀWỌN ORIN TÁ A Ó KỌ : 201 , 132
Anything Jehovah’s Word foretells always comes true .
Gbogbo ohun tí Bíbélì bá sọ tẹ́lẹ̀ ló máa ń ṣẹ .
That is the very essence of reasonableness ​ — being fair , considerate , and yielding without compromising Bible principles .
Ohun tó ń jẹ́ ìfòyebánilò gan - an nìyí , ìyẹn ni pé kéèyàn jẹ́ ẹni tí kì í ṣojúsàájú , tó ń gba tàwọn ẹlòmíràn rò , tó sì ń fara mọ́ èrò wọn láìjẹ́ pé èèyàn tẹ ìlànà Bíbélì lójú .
Ó fi kún un pé : “ Kì í ṣe pé ọ̀rọ̀ náà á wá rọrùn pátápátá láti máa sọ o , àmọ́ jíjùmọ̀ sọ̀rọ̀ fàlàlà ló ń jẹ́ kí ìdílé Kristẹni wà lálàáfíà . ” [ Àwọn Àlàyé ìsàlẹ̀ ìwé ]
Written : By some 40 writers over about 1,600 years , from 1513 B.C.E . to about 98 C.E .
Àwọn tí ó kọ ọ́ : Nǹkan bí ogójì [ 40 ] ọkùnrin ló kọ Bíbélì .
Nítorí náà , a kì í lọ́wọ́ sí irú àwọn àṣà bẹ́ẹ̀ .
Oppression and injustices abound today .
Ìwà àìṣòdodo àti ìnilára pọ̀ gan - an nínú ayé lónìí .
Seoul , Korea , 1963
1963 ní ìlú Seoul , ilẹ̀ Korea
[ Pictures on page 31 ]
[ Àwọn àwòrán tó wà ní ojú ìwé 29 ]
Everlasting life on earth will be possible for him through the resurrection .
Ó máa ṣeé ṣe fún un láti ní ìyè àìnípẹ̀kun lórí ilẹ̀ ayé nípasẹ̀ àjíǹde .
*
*
1 Peter 3 : ․ ․ ․
Mátíù 5 : ․ ․ ․
You still have life , one another , and your friends . ”
Ẹ̀mí yín ṣì wà , ẹ ṣì wà fún ara yín , àwọn ọ̀rẹ́ ṣì wà fún yín pẹ̀lú . ”
His bride must also be fittingly attired for the occasion .
Ìyàwó náà alára gbọ́dọ̀ múra lọ́nà tó bá ayẹyẹ ìgbéyàwó wọn mu .
European Court Upholds Conscientious Objection ( V . Bayatyan ) , 11 / 1
Máa Hùwà Bí Ẹni Tó Kéré Jù , 11 / 15
In Israel , music played yet other roles .
Àwọn nǹkan pàtàkì míì tún wà tí wọ́n máa ń fi orin ṣe nílẹ̀ Ísírẹ́lì .
2 TIMOTHY 3 : 3
2 TÍMÓTÌ 3 : 3
( b ) In what way do we demonstrate that we love Jesus ?
( b ) Ọ̀nà wo la gbà ń fi hàn pé a nífẹ̀ẹ́ Jésù ?
But when they see how shallow and cold the world really is , they may return .
Àmọ́ nígbà tí wọ́n bá rí i bí ayé ṣe rí , pé kò sí nǹkan kan nínú rẹ̀ àfi ìwà ìkà , wọ́n lè padà wá .
“ Forgetting the things behind and stretching forward to the things ahead . ” ​ — PHIL .
“ Ní gbígbàgbé àwọn ohun tí ń bẹ lẹ́yìn àti nínàgà sí àwọn ohun tí ń bẹ níwájú . ” — FÍLÍ .
Today , as we encourage others to share in the work of making disciples , we imitate Jesus .
Jésù là ń fara wé lóde òní , bá a ṣe ń gba àwọn ẹlòmíràn níyànjú pé kí wọ́n máa ṣe iṣẹ́ sísọni di ọmọ ẹ̀yìn .
He courageously spoke the truth and had absolutely no fear of man .
Ó máa ń fìgboyà sọ òtítọ́ ó sì dájú ṣáká pé kò bẹ̀rù èèyàn .
To be sure , our Creator , whom the Bible calls “ the happy God , ” wants us to lead happy , successful lives .
Dájúdájú , Ẹlẹ́dàá wa tí Bíbélì pè ní “ Ọlọ́run aláyọ̀ , ” náà ò fẹ́ ká máa kárí sọ tàbí ká máa rùnpà .
Never before has the name Jehovah been given such wide publicity in Germany .
Kò tíì sígbà tí wọ́n polongo orúkọ Jèhófà tó báyẹn rí nílẹ̀ Jámánì .
However , many sites on the Internet are morally and spiritually dangerous .
Àmọ́ ṣá o , ọ̀pọ̀ àwọn ìkànnì orí Íńtánẹ́ẹ̀tì léwu gan - an fún àwọn tó fẹ́ láti máa ṣe ohun tó tọ́ , tí wọn kò sì fẹ́ kí ohunkóhun ba àjọṣe wọn pẹ̀lú Ọlọ́run jẹ́ .
Have we not seen that Jehovah’s mercy and patience are far greater than we at first thought ?
Ṣebí a ti rí i pé àánú àti sùúrù Jèhófà ga ju bá a ṣe rò lọ , àbí bẹ́ẹ̀ kọ́ ?
For Christ’s true followers , that involves their whole way of life , including their attitude toward money , secular work , entertainment , worldly customs and celebrations , and marriage and other relationships with fellow humans .
Ohun tá a sọ yìí máa ń hàn nínú bí àwọn ojúlówó ọmọlẹ́yìn Kristi ṣe ń gbé ìgbé ayé wọn , tó fi mọ́ ọwọ́ tí wọ́n fi ń mú ọ̀ràn owó , iṣẹ́ oúnjẹ òòjọ́ , eré ìnàjú , àwọn àṣà àti ayẹyẹ ayé , ìgbéyàwó àti àjọṣe wọn pẹ̀lú àwọn èèyàn .
Mount Tabor
Òkè Ńlá Tábórì
When Christians voluntarily simplify their lives , not merely to slow down and enjoy life but to have a greater share in this meaningful work , they are “ treasuring up for themselves a fine foundation for the future ” in God’s promised new world .
Báwọn Kristẹni bá ń gbé ìgbé ayé tó wà níwọ̀ntúnwọ̀nsì , tí kì í wulẹ̀ ṣe pé wọ́n dín ohun tí wọ́n ń ṣe kù kí wọ́n ṣì lè máa dọ́gbọ́n jayé , àmọ́ tó jẹ́ pé ṣe ni wọ́n túbọ̀ ń kópa nínú iṣẹ́ tó nítumọ̀ yìí , a jẹ́ pé wọ́n ń “ to ìṣúra ìpìlẹ̀ tí ó dára lọ́pọ̀lọpọ̀ jọ fún ara wọn de ẹ̀yìn ọ̀la ” nínú ayé tuntun Ọlọ́run nìyẹn .
Could the earth’s resources be distributed more evenly ?
Ǹjẹ́ wọ́n lè pín àwọn ohun àmúṣọrọ̀ ayé lọ́gbọọgba ?
Angels ​ — How They Affect Us
Ohun Tí Àwọn Áńgẹ́lì Ń Ṣe fún Wa
By rejecting discipline , the ridiculer only makes himself ridiculous .
Nípa kíkọ ìbáwí , ńṣe ni olùyọṣùtì náà wulẹ̀ ń sọ ara rẹ̀ di ẹni yẹ̀yẹ́ .
They were in operation until mills driven by steam and other sources of energy gradually made all other power sources obsolete .
Àwọn ẹ̀rọ náà ò sì kúrò lọ́jà títí táwọn ẹ̀rọ tó ń lo ooru gbígbóná àtàwọn ohun àmúṣagbára mìíràn fi wá dọ́gbọ́n gbá gbogbo àwọn orísun agbára yòókù wọlé .
sweets ( rarely ; limit to 75 calories a day )
Oúnjẹ Ọlọ́ràá Òróró ólífì , oríṣiríṣi ẹ̀pà ,
Now I began to appreciate more fully God’s qualities .
Bí mo ṣe bẹ̀rẹ̀ sí í mọyì àwọn ànímọ̀ Ọlọ́run díẹ̀díẹ̀ nìyẹn .
Enemy archers hit their mark , and he tells his servants : “ Take me down , for I have been very severely wounded . ”
Àwọn ọ̀tá ta á lọ́fà , ó sì sọ fún àwọn ìránṣẹ́ rẹ̀ pé : “ Ẹ gbé mi sọ̀ kalẹ̀ , nítorí mo ti gbọgbẹ́ gidigidi . ”
One worthwhile goal is to improve in our Bible reading .
Mímú kí Bíbélì kíkà wa túbọ̀ dára sí i jẹ́ góńgó kan tó yẹ kéèyàn lépa .
Ever since then , Satan has exercised unseen influence over human affairs .
Látìgbà náà ni Sátánì ti fara pa mọ́ tó ń dá sí ọ̀ràn ẹ̀dá èèyàn .
Our Readers Ask . . .
Àwọn Òǹkàwé Wa Béèrè Pé . . .
▪ Be Long - Suffering .
▪ Ní Ìpamọ́ra .
Think about this : If Jehovah cares for the birds , how much more so does he care for you who love him and have given yourself to him ?
Ó fẹ́ láti máa tọ́jú rẹ torí pé o fẹ́ràn rẹ̀ o sì ti ya ara rẹ sí mímọ́ fún un .
“ The Father Incomprehensible , the Son Incomprehensible , and the Holy Ghost Incomprehensible . ” ​ — The Athanasian Creed , describing the Trinity taught by many churches of Christendom .
“ Bàbá jẹ́ Aláìṣeélóye , Ọmọ jẹ́ Aláìṣeélóye , Ẹ̀mí Mímọ́ náà jẹ́ Aláìṣeélóye . ” — Ìjẹ́wọ́ Ìgbàgbọ́ Athanasia , tó ń ṣàlàyé Mẹ́talọ́kan tí ọ̀pọ̀ ṣọ́ọ̀ṣì ń kọ́ni .
This can happen only if we express our own feelings to God instead of reciting memorized prayers .
Kìkì tí a bá sọ àwọn èrò inú tiwa fúnra wa fún Ọlọ́run , dípò táa ó fi máa ka àwọn àdúrà àkọ́sórí nìkan ni èyí fi lè ṣeé ṣe .
They indicate that we are living in “ the last days ” of this wicked system , which the Bible foretold would be characterized by “ critical times hard to deal with . ”
Wọ́n ń fi hàn pé “ àwọn ọjọ́ ìkẹyìn ” ètò nǹkan búburú yìí la wà , èyí tí Bíbélì sọ àsọtẹ́lẹ̀ pé “ àwọn àkókò lílekoko tí ó nira láti bá lò ” la ó fi dá a mọ̀ .
For example , the Bible tells about an important man in the Syrian army who had the bad disease leprosy .
Bí àpẹẹrẹ , Bíbélì sọ fún wa nípa ọkùnrin pàtàkì kan nínú àwọn ọmọ ogun Síríà , tó ní àrùn burúkú kan , ìyẹn àrùn ẹ̀tẹ̀ .
Before you were married , likely you both set aside time to do things together .
Kẹ́ ẹ tó ṣègbéyàwó , ó ṣeé ṣe kó jẹ́ pé ẹ máa ń ya àwọn àkókò kan sọ́tọ̀ tẹ́ ẹ fi máa ń ṣe àwọn nǹkan kan pa pọ̀ .
Have you at times felt all alone in dealing with a difficult situation ?
Ǹjẹ́ ó ti ṣe ẹ́ rí bí i pé ìwọ nìkan lo ń fàyà rán ìṣòro rẹ ?
He will earn his wife’s respect by exercising his headship in a compassionate manner .
Ìyàwó rẹ̀ á máa bọ̀wọ̀ fún un tó bá ń lo ipò orí rẹ̀ lọ́nà pẹ̀lẹ́tù .
Ṣe ni inú wa ń dùn bíi ti Arákùnrin Chantel tó wá láti ilẹ̀ Faransé , arákùnrin yìí sọ pé : “ Ẹni tó lágbára jù lọ láyé àti lọ́run , Ẹlẹ́dàá ohun gbogbo , Ọlọ́run aláyọ̀ , sọ fún mi pé : ‘ Lọ !
The psalmist David , who himself was a strong and courageous man , said : “ Be agitated , but do not sin .
Onísáàmù náà , Dáfídì tó jẹ́ akíkanjú ọkùnrin àti onígboyà sọ pé : “ Kí inú yín ru , ṣùgbọ́n ẹ má ṣẹ̀ .
Therefore , to safeguard our friendship with him , Jehovah instructs us to avoid being self - centered .
Nítorí náà , kí àjọṣe àárín àwa àti Jèhófà má bàa yingin , ó gbà wá nímọ̀ràn pé ká yẹra fún dídi onímọtara - ẹni - nìkan .
The prophet continues to describe Jehovah’s actions in destroying His enemies .
Wòlíì náà ń báa lọ láti ṣàpèjúwe bí Jèhófà ṣe ń pa àwọn ọ̀tá Rẹ̀ run .
Àmọ́ ńṣe ni ìṣòro ọ̀hún tún wá pọ̀ sí i nígbà tá a bẹ̀rẹ̀ sí í bímọ .
AMERICAS : In 2012 , in Brazil , 25 people were convicted of using public funds to buy political support .
GÚÚSÙ AMẸ́RÍKÀ : Lọ́dún 2012 , lórílẹ̀ - èdè Brazil , èèyàn mẹ́ẹ̀ẹ́dọ́gbọ̀n [ 25 ] ló jẹ̀bi ẹ̀sùn tí wọ́n fi kàn wọ́n pé wọ́n fi owó ìlú ra ìbò .
Jehovah allowed the Babylonians to overthrow Jerusalem and to take his people into captivity .
Jèhófà fàyè gba àwọn ará Bábílónì láti pa Jerúsálẹ́mù run , kí wọ́n sì kó àwọn èèyàn rẹ̀ nígbèkùn .
36 : 2 , 3 , 22 .
36 : 2 , 3 , 22 .
Although my family offered us free land and a house , Ralph declined .
Bó tilẹ̀ jẹ́ pé ìdílé mi fún wa ní ilẹ́ àti ilé lọ́fẹ̀ẹ́ , Ralph kọ̀ ọ́ .
Liken one thing to another, liken one matter to another; forgive and forget and earn people's praise. Rather than permit an offence to recall earlier ones, one should forgive and forget. This is a variant of Àfiohunwé-ohun...
Fi ohun wé ohun, fi ọ̀ràn wé ọ̀ràn;fi ọ̀ràn jì ká yìn ọ́.
Pum , Jan , Dries , and Otto , four Christian elders living in the Netherlands , have much in common .
Àwọn mẹ́rin yìí , Pum , Jan , Dries àti Otto , tí wọ́n jẹ́ Kristẹni alàgbà ní Netherlands jọ ara wọn lọ́nà tó pọ̀ .
It certainly is possible for Christians to find joy in marriage .
Ó dájú pé àwọn Kristẹni lè jẹ́ kí ayọ̀ wà nínú ìdílé wọn .
I find real satisfaction in knowing that all my efforts will benefit others spiritually and will bring praise to Jehovah . ”
Mo ní ojúlówó ìtẹ́lọ́rùn ní mímọ̀ pé gbogbo ìsapá mi yóò ṣàǹfààní fún àwọn ẹlòmíràn nípa tẹ̀mí , yóò sì mú ìyìn bá Jèhófà . ”
Jehovah is the Creator , the heavenly Sovereign , worthy of all worship and praise .
Jèhófà ni Ẹlẹ́dàá àti Ọba Aláṣẹ ọ̀run , ẹni tí gbogbo ìjọsìn àti ìyìn tọ́ sí .
PAGE 12
OJÚ ÌWÉ 12
Many get baptized at a young age , and they go on to be faithful to Jehovah .
Àwọn kan lè ṣèrìbọmi nígbà tí wọ́n ṣì kéré , kí wọ́n sì máa fòótọ́ sin Jèhófà nìṣó .
Some names in this article have been changed .
A ti yí àwọn orúkọ kan pa dà nínú àpilẹ̀kọ yìí .
Paul’s warm words of commendation must have encouraged those Hebrew Christians greatly .
Ó dájú pé bí Pọ́ọ̀lù ṣe gbóríyìn fún àwọn Kristẹni tó jẹ́ Hébérù yìí máa fún wọn ní ìṣírí gan - an .
How can we profitably use time spent waiting , following whose examples ?
Báwo la ṣe lè lo àkókò táa fi ń dúró lọ́nà tó mérè wá , ní títẹ̀lé àpẹẹrẹ àwọn wo ?
It went on to say : “ On Christmas Eve , 24 December , Adam and Eve would be commemorated with the highly popular episode of the Tree of the earthly Paradise . . .
Àpilẹ̀kọ yẹn ń bá a lọ pé : “ Alẹ́ ọjọ́ tó ṣáájú Kérésìmesì , ìyẹn December 24 , ni wọ́n máa ń fi ìtàn olókìkí nípa Igi tó wà nínú Párádísè orí ilẹ̀ ayé ṣèrántí Ádámù àti Éfà . . .
Yet , a person who chooses to do so should be alert to certain dangers .
Àmọ́ , bẹ́nì kan bá wá pinnu pé òun fẹ́ gbààwẹ̀ , ó máa dáa kó fara balẹ̀ ronú lórí àwọn ohun tí kì í jẹ́ kínú Ọlọ́run dùn sáwọn ààwẹ̀ kan .
What quality is needed for one to “ remain in [ Jesus ’ ] word ” ?
Ànímọ́ wo lẹnì kan gbọ́dọ̀ ní tó bá fẹ́ “ dúró nínú ọ̀rọ̀ [ Jésù ] ” ?
□ John 18 : 28 - 19 : 42
▪ Ó kú ní nǹkan bí □ Jòhánù 18 : 28 - 40
Apart from our personal happiness , these issues affect our standing before Jehovah God .
Àti pé gbogbo Kristẹni tó ṣègbéyàwó àtàwọn tí kò ṣègbéyàwó ló ń dojú kọ ìdẹwò láti ṣèṣekúṣe .
All your senses ​ — sight , hearing , smell , touch , and taste — ​ function perfectly .
O lè ríran kedere , o lè gbọ́ràn , o lè gbóòórùn , o lè mọ bí nǹkan ṣe rí tó o bá fọwọ́ kàn án tàbí tó o bá tọ́ ọ wò .
For example , while ardently pursuing wealth , people often sacrifice relationships with family and friends .
Bí àpẹẹrẹ , nígbà táwọn èèyàn bá ń fi gbogbo ara lépa ọrọ̀ , wọ́n sábà máa ń fi àjọṣe tí wọ́n ní pẹ̀lú ìdílé àtàwọn ọ̀rẹ́ wọn dí i .
2 : 9 .
2 : 9 .
Imagine monkeys chattering and screeching from the tops of date palms and fig trees .
Ó lè máa rántí àwọn ilẹ̀ olókè tó ń bẹ ní Hébúrónì ìlú rẹ̀ , àmọ́ ní báyìí , wọ́n ti rin ọgọ́rọ̀ọ̀rún máìlì kọjá ibẹ̀ , wọn sì ti wà ní ìlú míì .
23 The Lure of Santeria
24 Àwọn Ewu Tó Wà Nínú Wíwọkọ̀ Ọ̀fẹ́ Kiri

No dataset card yet

New: Create and edit this dataset card directly on the website!

Contribute a Dataset Card
Downloads last month
1
Add dataset card