ending1
stringlengths
4
149
ending2
stringlengths
5
156
startphrase
stringlengths
7
179
labels
int64
0
1
split
stringclasses
7 values
Àbíkẹ́ mọ iṣẹ́ agbẹ̀bí dáadáa
Àbíkẹ́ ò mọ iṣẹ́ agbẹ̀bí rárá
Àbíkẹ́ ní òye tó dájú nípa iṣẹ́ agbẹ̀bí bí i àwọn dọ́kítà ilẹ̀ òkèrè
0
yo
Àbíkẹ́ mọ iṣẹ́ agbẹ̀bí dáadáa
Àbíkẹ́ ò mọ iṣẹ́ agbẹ̀bí rárá
Àbíkẹ́ ní òye kukurú nípa iṣẹ́ agbẹ̀bí bí i àwọn dọ́kítà ilẹ̀ òkèrè
1
yo
Aṣọ funfun tí ó wọ̀ ti dọ̀tí
Aṣọ funfun tí ó wọ̀ mọ́ gan
Aṣọ àlà tí ó wọ̀ ti pọ́n bí i ẹni tó kó sínú ẹrọ̀fọ̀
1
yo
Aṣọ funfun tí ó wọ̀ ti dọ̀tí
Aṣọ funfun tí ó wọ̀ mọ́ gan
Aṣọ àlà tí ó wọ̀ mọ́ ju ẹyín tí mo ṣẹ̀ṣẹl fọ̀ láàárọ̀ yìí lọ
0
yo
Wèré ni Òjó
Òjó kì í ṣe wèrè
Oní gángàngán ni Òjó gbogbo wa la mọ̀ bẹ́ẹ̀
1
yo
Wèré ni Òjó
Òjó kì í ṣe wèrè
Apẹja ni Òjó gbogbo wa la mọ̀ bẹ́ẹ̀
0
yo
Kò sí ariwo nínu yàrá ìdánwò náà
Ariwo ti pọ̀jù nínu yàrá ìdánwò nàá
Inú yàrá ìdánwò nàá palọ́lọ́ bí i itẹ́ òkú
0
yo
Kò sí ariwo nínu yàrá ìdánwò náà
Ariwo ti pọ̀jù nínu yàrá ìdánwò nàá
Inú yàrá ìdánwò nàá rí bí i ọjà Oṣòdì
1
yo
Òtútù mú ìyá àgbà
Orú mú ìyá àgbà
Gbogbo ara ìyá àgbà ti gan sínú ilé bí i òkú tó wà nínu yìnyín
0
yo
Òtútù mú ìyá àgbà
Orú mú ìyá àgbà
Gbogbo ara ìyá àgbà kò gan sínú ilé
1
yo
Àlàmù rí òkun náà tó ń ru
Àlàmù rí òkun náà tó dákẹ́
Àlàmú rí òkun náà tó ń kọrin lásìkò tó ń bọ̀ láti ibi iṣẹ́
0
yo
Àlàmù rí òkun náà tó ń ru
Àlàmù rí òkun náà tó dákẹ́
Àlàmú rí òkun náà tó ń yọ iná lásìkò tó ń bọ̀ láti ibi iṣẹ́
1
yo
Àgbẹ̀ náà ti ká gbogbo èso tó wà lóri igi nàá
Àgbẹ̀ náà ò ká èso kankan lóri igi nàá
Àgbẹ̀ náà ti kó gbogbo ọmọ tí igi nàá bí lánàá
0
yo
Àgbẹ̀ náà ti ká gbogbo èso tó wà lóri igi nàá
Àgbẹ̀ náà ò ká èso kankan lóri igi nàá
Àgbẹ̀ náà pa gbogbo ọmọ tí igi nàá bí lánàá
1
yo
Arábìnrin náà ò lójú ara
Arábìnrin lójú ara
Lákíríboto ni arábìnrin tí ọ̀gá ṣẹ̀ṣẹ̀ gbà sí ẹnu iṣẹ́
1
yo
Arábìnrin náà ò lójú ara
Arábìnrin lójú ara
Ọmọdé ni arábìnrin tí ọ̀gá ṣẹ̀ṣẹ̀ gbà sí ẹnu iṣẹ́
0
yo
Àṣàbí ò rọ́mọ bí fún ọgbọ̀n ọdún
Àṣàbí bí ọmọ tó pọ̀ fún ọgbọ̀n ọdún
Àgàn ni Àṣàbí fún ọgbọ̀n ọdún
1
yo
Àṣàbí ò rọ́mọ bí fún ọgbọ̀n ọdún
Àṣàbí bí ọmọ tó pọ̀ fún ọgbọ̀n ọdún
Abiyamọ ni Àṣàbí fún ọgbọ̀n ọdún
0
yo
Ìdòwú ti pẹ́ gan nínú iṣẹ́ ọdẹ
Ìdòwú ṣẹ̀ṣẹ̀ bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ ọdẹ
Láti kéreké ni Ìdòwú tí ń ṣe iṣẹ́ ọdẹ bí i bàbá rẹ̀
0
yo
Ìdòwú ti pẹ́ gan nínú iṣẹ́ ọdẹ
Ìdòwú ṣẹ̀ṣẹ̀ bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ ọdẹ
Láti kéreké ni Ìdòwú kò ti nífẹ̀ẹ́ si iṣẹ́ ọdẹ ṣíṣe
1
yo
Orí Gbádébọ̀ tóbi gan
Orí Gbádébọ̀ kò tóbi
Orí Gbádébọ̀ rí bí i orí òkè olúmọ
1
yo
Orí Gbádébọ̀ tóbi gan
Orí Gbádébọ̀ kò tóbi
Orí Gbádébọ̀ kò rí bí i orí òkè olúmọ
0
yo
Ẹsẹ Bólájí gùn gan
Ẹsẹ Bólájí kéré gan
Ẹsẹ̀ Bólájí gùn bí i ọ̀pá Ọ̀rànmíyàn
1
yo
Ẹsẹ Bólájí gùn gan
Ẹsẹ Bólájí kéré gan
Ẹsẹ̀ Bólájí rẹwà bí i tọmọ ìkókó
0
yo
Ó gbọ́ èdè Yorùbá dáadáa
Kò gbọ́ èdè Yorùbá rárá
Èdè Yorùbá ẹnu rẹ̀ dánmọ́rán bí i tàwọn ará Ọ̀yọ́
0
yo
Ó gbọ́ èdè Yorùbá dáadáa
Kò gbọ́ èdè Yorùbá rárá
Èdè Yorùbá ẹnu rẹ̀ kò dánmọ́rán bí i tàwọn Ẹ̀gùn
1
yo
Gàrí náà kan
Gàrí náà ò kan
Gàrì náà kan bí i omi ògì
0
yo
Gàrí náà kan
Gàrí náà ò kan
Gàrì náà korò bí i omi ògì àná
1
yo
Eyin rẹ̀ mọ́
Eyin rẹ̀ dọ̀tí
Eyín rẹ̀ funfun bí i ẹyẹ àdàbà
0
yo
Eyin rẹ̀ mọ́
Eyin rẹ̀ dọ̀tí
Eyín rẹ̀ kò funfun bí i ẹyẹ àdàbà
1
yo
Orí Adékúnlé pọ́n
Orí Adékúnlé kò pọ́n
Adékúnlé dárípọ́ bí i orí aláǹgbá
0
yo
Orí Adékúnlé pọ́n
Orí Adékúnlé kò pọ́n
Adékúnlé ti fọ́ lórí níbi tó ti lọ jà
1
yo
Bọ́látitó máa ń dá nìkan wà
Bọ́látitó máa ń wà pẹ̀lú àwọn ọ̀pọ̀ ènìyàn
Àso erin ni Bọ́látitó
1
yo
Bọ́látitó máa ń dá nìkan wà
Bọ́látitó máa ń wà pẹ̀lú àwọn ọ̀pọ̀ ènìyàn
Ọlọ́yàyà ni Bọ́látíto
0
yo
Eégún ni Àjàní
Àjàní kì í ṣe Eégún
Ará ọ̀run ni Àjàní
0
yo
Eégún ni Àjàní
Àjàní kì í ṣe Eégún
Àjàní kì i ṣe Ará ọ̀run
1
yo
Kò sí ẹni tó mọ ìṣe Àbẹ̀kẹ́
Gbogbo wa la mọ ìṣe Àbẹ̀kẹ́
Paramọ́lẹ̀ ni Àbẹ̀kẹ́
1
yo
Kò sí ẹni tó mọ ìṣe Àbẹ̀kẹ́
Gbogbo wa la mọ ìṣe Àbẹ̀kẹ́
Àbẹ̀kẹ́ kì i ṣe Paramọ́lẹ̀
0
yo
Àgbékẹ́ máa ń fẹnu ba èèyàn jẹ́
Àgbékẹ́ máa ń fẹnu kọrin
Ẹlẹ́nu ẹyẹ ni Àgbékẹ́
1
yo
Àgbékẹ́ máa ń fẹnu ba èèyàn jẹ́
Àgbékẹ́ máa ń fẹnu yin ènìyàn
Aládúrà ni Àgbékẹ́
0
yo
Ọmọ náà mọ Ifá dáadáa
Wọ́n ti kọ Ifá fún ọmọ náà sínú ìwè
Ọmọ náà gbọ́ Ifá, ó mọ nú ìgbín nínú ìkàrahun bí í abọrẹ̀ agboolé wa
0
yo
Ọmọ náà mọ Ifá dáadáa
Wọ́n ti kọ Ifá fún ọmọ náà sínú ìwè
Ọmọ náà kò mọ nǹkankan nípa Ifá
1
yo
Àṣírí Gbádégẹṣin àti àbúrò rẹ̀ ti tú
Àṣírí Gbádégẹṣin àti àbúrò ti bò
Àkàrà Gbádégẹṣin àti àbúrò rẹ̀ ti tú sépo bí i ti bàbá wọn tó wà lẹ́wọ̀n
0
yo
Àṣírí Gbádégẹṣin àti àbúrò rẹ̀ ti tú
Àṣírí Gbádégẹṣin àti àbúrò ti bò
Àkàrà Gbádégẹṣin àti àbúrò rẹ̀ kò tú sépo
1
yo
Àbẹ̀ní se oríṣiríṣi ọbẹ̀ lánàá
Àbẹ̀ní kò se oríṣiríṣi ọbẹ̀ lánàá
Àbẹ̀ní se onírurú ọbẹ̀ lánàá bí i àwọn tó ń dáná olópò
0
yo
Àbẹ̀ní se oríṣiríṣi ọbẹ̀ lánàá
Àbẹ̀ní kò se oríṣiríṣi ọbẹ̀ lánàá
Àbẹ̀ní se onírurú ọbẹ̀ tí kò dùn lánàá.
1
yo
Òjò náà sú lánàá ó tó ago mọ́kànlá kó tó rọ̀
Òjò náà kò sú lánàá kò sì rọ̀ ní ago mọ́kànlá
Ojú ọ̀run náà lóyún omi nǹkan bí i ago mọ́kànlá ló tó bímọ
0
yo
Òjò náà sú lánàá ó tó ago mọ́kànlá kó tó rọ̀
Òjò náà kò sú lánàá kò sì rọ̀ ní ago mọ́kànlá
Ojú ọ̀run náà ò lóyún omi
1
yo
Òòrùn àná mú gan
Òòrùn àná kò mú rárá
Òòrun àná ta ènìyàn lára bí i iná àdògán
1
yo
Òòrùn àná mú gan
Òòrùn àná kò mú rárá
Òòrun àná kò ta ènìyàn lára
0
yo
Ojú Yẹmí le gan
Ojú Yẹmí kò le rárá
Ojú Yẹmí le bí i ojú ọ̀daràn kò sí eni tó lè ba sọ̀rọ̀
1
yo
Ojú Yẹmí le gan
Ojú Yẹmí kò le rárá
Ojú Yẹmí ni àwọn ọmọge fẹ́ rí
0
yo
Aṣọ Títílayọ̀ kò dára rárá
Aṣọ Títílayọ̀ dára gan
Aṣọ Títílayọ̀ rí bí i aṣọ egbéré
1
yo
Aṣọ Títílayọ̀ kò dára rárá
Aṣọ Títílayọ̀ dára gan
Aṣọ Títílayọ̀ rí bí i aṣọ ọba ilé ifẹ̀
0
yo
Afọlábí ò lè gbé láàárín àwọn ènìyàn
Afọlábí lè gbé láàárín àwọn ènìyàn
Adẹ́tẹ̀ ni Afọlábí
1
yo
Afọlábí ò lè gbé láàárín àwọn ènìyàn
Afọlábí lè gbé láàárín àwọn ènìyàn
Afọlábí kì i ṣe Adẹ́tẹ̀
0
yo
Adé ń pariwo gan
Adé kò pariwo rárá
Adé ń pariwo bí i eni tí ajá bùjẹ
1
yo
Adé ń pariwo gan
Adé kò pariwo rárá
Adé ń pariwo bí i eni tí ó sù lọ fọnfọn
0
yo
Àdìsá pọn omi púpọ̀
Omi díẹ̀ ni Àdìsá pọn
Ike omi ọgọ́rùn-ún ni Àdìsá pọn kó tó lọ sí ilé ìwé láàárọ̀ yìí
0
yo
Àdìsá pọn omi púpọ̀
Omi díẹ̀ ni Àdìsá pọn
Ike omi kan ṣoṣo ni Àdìsá pọn kó tó lọ sí ilé ìwé láàárọ̀ yìí
1
yo
Olùdíje mọ eré sá gan
Olùdíje náà kò sáré ba ṣe fẹ́
Olùdíje náà sáré bí i atẹ́gùn
0
yo
Olùdíje mọ eré sá gan
Olùdíje náà kò sáré ba ṣe fẹ́
Olùdíje náà sáré bí i ìgín
1
yo
Àpò náà wúwo gan
Àpò náà fuyẹ́
Àpò náà wúwo bí i àpo tó kún fún òkúta ńlá
0
yo
Àpò náà wúwo gan
Àpò náà fuyẹ́
Àpò náà kò wúwo rárá
1
yo
Ètè rẹ̀ ti dúdú jù
Ètè rẹ̀ pupa
Ètè rẹ̀ dúdú bí i ètè ẹni tó ń fa igbó
1
yo
Ètè rẹ̀ ti dúdú jù
Ètè rẹ̀ pupa
Ètè rẹ̀ kò dúdú bí i ètè ẹni tó ń fa igbó
0
yo
Fọlárìn ò jẹun bàṣùbàṣù
Fọlárìn bá ẹlẹ́dẹ̀ ṣeré
Fọlárìn jẹun bí i ẹlẹ́dẹ̀
1
yo
Fọlárìn ò jẹun bàṣùbàṣù
Fọlárìn bá ẹlẹ́dẹ̀ ṣeré
Fọlárìn ò jẹun bí i ẹlẹ́dẹ̀
0
yo
Ayọ̀mídé ò lẹ̀ rìn dáadáa lẹ́yìn abọ́ ẹ̀bà méjìlá
Ayọ̀mídé rìn dáada lẹ́yìn abọ́ ẹ̀bà méjìlá
Ayọ̀mídé jẹ abọ́ ẹ̀bà méjìlá, ó wá ń gbẹ́sẹ̀ bí i olóyún tó ń rọbí
1
yo
Ayọ̀mídé ò lẹ̀ rìn dáadáa lẹ́yìn abọ́ ẹ̀bà méjìlá
Ayọ̀mídé rìn dáada lẹ́yìn abọ́ ẹ̀bà méjìlá
Ayọ̀mídé ò lè jẹ abọ́ ẹ̀bà méjìlá, kò sì rìn bí i olóyún
0
yo
Eléégún ni Dánṣọfúnjó
Oní ìlù ni Dánṣọfúnjó
Ọlọ́jẹ̀ ni Dáṣọfúnjó
0
yo
Eléégún ni Dánṣọfúnjó
Oní ìlù ni Dánṣọfúnjó
Oníjó ni Dáṣọfúnjó
1
yo
Igi náà tóbi gan
Igi náà kò tóbi gan
Igi tí wọ́n fi pa ejó náà rí ràbàtà bí i igi ìrókò
0
yo
Igi náà tóbi gan
Igi náà kò tóbi gan
Igi tí wọ́n fi pa ejó náà rí sọrọ
1
yo
Nǹkan ọmọ ọkùnrin bàbá Bọ́lájí ti kéré jù
Nǹkan ọmọ ọkùnrin bàbá Bọ́lájí ti tóbi jù
Ìyá Bọ́lájí sọ pé nǹkan ọmọ ọkùnrin bàbá Bọ́lájí rí bí i tọmọ ìkókó
0
yo
Nǹkan ọmọ ọkùnrin bàbá Bọ́lájí ti kéré jù
Nǹkan ọmọ ọkùnrin bàbá Bọ́lájí ti tóbi jù
Ìyá Bọ́lájí sọ pé nǹkan ọmọ ọkùnrin bàbá Bọ́lájí ṣiṣẹ́ dáadáa
1
yo
Mo fẹ́ ní ìmọ̀ ti ọ̀jọ̀gbọ̀n Wọlé Ṣóyinká ní
Ọ̀jọ̀gbọ̀n Wọlé Ṣóyinká ò ní ìmọ̀ tí mo ní
Ró mi láṣọ ìmọ̀ bí i ọ̀jọgbọ̀n Wọlé Ṣóyinká
0
yo
Mo fẹ́ ní ìmọ̀ ti ọ̀jọ̀gbọ̀n Wọlé Ṣóyinká ní
Ọ̀jọ̀gbọ̀n Wọlé Ṣóyinká ò ní ìmọ̀ tí mo ní
Bàbá mi ni ọ̀jọ̀gbọ́n Wọlé Ṣóyinká
1
yo
Ọmọ ọdún mẹ́fà náà mọ ìlú lù dáadáa
Ọmọ ọdún mẹ́fà náà kò mọ ìlú lù rárá
Ọmọ ọdún mẹ́fà náà lu ìlù bí i ẹni tí wọ́n bí sí ìdílé àyàn
0
yo
Ọmọ ọdún mẹ́fà náà mọ ìlú lù dáadáa
Ọmọ ọdún mẹ́fà náà kò mọ ìlú lù rárá
Ọmọ ọdún mẹ́fà náà gbé ìlù kọ́rùn bí i ẹni tí wọ́n bí sí ìdílé àyàn
1
yo
Mo nífẹ̀ẹ́ Adédoyin gan
Mo ò nífẹ̀ẹ́ Adédoyin rárá
Ìfẹ́ Adédoyin pamí bí i ọtí
0
yo
Mo nífẹ̀ẹ́ Adédoyin gan
Mo ò nífẹ̀ẹ́ Adédoyin rárá
Ìfẹ́ Adédoyin ti yọ́ kúrò lọ́kàn mi
1
yo
Àbẹ̀ún wọ aṣọ púpọ̀
Àbẹ̀ún wọ aṣọ díẹ̀
Àbẹ̀ún kó sí aṣọ bí i ẹni tí òtútù ń mú
0
yo
Àbẹ̀ún wọ aṣọ púpọ̀
Àbẹ̀ún wọ aṣọ díẹ̀
Àbẹ̀ún kó sí́ aṣọ tuntun tó rà
1
yo
Ayé ò lọ lóju kan
Ọ̀nà kan layé wà
Ayé ò lọ bí i ọ̀pá ìbọn
0
yo
Ayé ò lọ lóju kan
Ọ̀nà kan layé wà
Ayé lọ bí i ọ̀pá òrúnmìlà
1
yo
Àdùnní tí ń ṣe orí ire
Orí burúkú ni Àdùnnní ṣe
Àdùnnị ṣẹ̀ṣẹ̀ bẹ̀rẹ̀ sí ní gun àkàbà orí ire rẹ
0
yo
Àdùnní tí ń ṣe orí ire
Orí burúkú ni Àdùnnní ṣe
Àdùnnị ṣẹ̀ṣẹ̀ bẹ̀rẹ̀ sí ní lọ ilé ìwé
1
yo
Tímìlẹ́yìn ṣe àṣeyọrí
Tímìlẹ́yìn ṣe òfò
Tìmílẹ́yìn kógo já níbi ìdánwò àṣekágbá
0
yo
Tímìlẹ́yìn ṣe àṣeyọrí
Tímìlẹ́yìn ṣe òfò
Tìmílẹ́yìn fìdí rẹmi níbi ìdánwò àṣekágbá
1
yo
Àmọ̀pé yára mí lọ sókè sílẹ̀
Àmọ̀pé mí lẹ́ẹ̀kan ṣoṣo
Àmọ̀pé mí gúlegúle bí i ajá tí ẹbí pa
0
yo
Àmọ̀pé yára mí lọ sókè sílẹ̀
Àmọ̀pé mí lẹ́ẹ̀kan ṣoṣo
Àmọ̀pé kò mí mọ.
1
yo
Àsàkẹ́ kò jókòó dáadáa
Àsàkẹ́ jókòó fẹ̀yìntì
Àṣàkẹ́ jókòó sórí àga bí i ẹni ti ìsó gún nídìí
0
yo
Àsàkẹ́ kò jókòó dáadáa
Àsàkẹ́ jókòó fẹ̀yìntì
Àṣàkẹ́ fọ́ àga tó ṣẹ̀ṣẹ̀ rà
1
yo
Ojú Ìgè kò rẹwà
Wọ́n fi ẹ̀rín sí ẹnu Ìgè
Ojú Ìgè rí bí i ojú eye àdán
1
yo
Ojú Ìgè kò rẹwà
Wọ́n fi ẹ̀rín sí ẹnu Ìgè
Ojú Ìgè kún fún ẹ̀rín àti ayọ
0
yo
Ó ń ranjú
Ó ń rẹ́rìn ín
Ó taná ojú bí i iná mọ́to ayọ́kẹ́lẹ́
0
yo
Ó ń ranjú
Ó ń rẹ́rìn ín
Ó taná ojú kò rí nǹkankan
1
yo
Ojú Fọlárìn ti fọ́
Fọlárìn ríran kedere
Ojú Fọlárìn ti relé dèé
0
yo
Ojú Fọlárìn ti fọ́
Fọlárìn ríran kedere
Ojú Fọlárìn ti tóbi jú
1
yo