ending1
stringlengths
4
149
ending2
stringlengths
5
156
startphrase
stringlengths
7
179
labels
int64
0
1
split
stringclasses
7 values
Ìdánwò náà le gan
Ìdánwò náà rọ̀
Ìdánwò tí Dúpé ṣe lánàá gbomi gan
1
yo
Ìdánwò náà le gan
Ìdánwò náà rọ̀
Ìdánwò tí Dúpé ṣe lánàá ò gbomi rárá
0
yo
Mo wo sinimá Aníkúlápó ní ọ̀pọ̀lọpọ̀ ìgbà
Mo wo sinimá Aníkúlápó lẹ́ẹ̀kan ṣoṣo
Mo wo sinimá Aníkúlápó nígbà igba
0
yo
Mo wo sinimá Aníkúlápó ní ọ̀pọ̀lọpọ̀ ìgbà
Mo wo sinimá Aníkúlápó lẹ́ẹ̀kan ṣoṣo
Sinimá Aníkúlápó tí mo wò kò dùn
1
yo
Ewé náà pọ́n gan
Ewé náà dúdú gan
Ewé nàá pọ́n bí i òdòdó
0
yo
Ewé náà pọ́n gan
Ewé náà dúdú gan
Ewé nàá ti sunko
1
yo
Rónmú pariwo ní àárọ̀ yìí
Rónmú se oúnjẹ
Rónmú dún bí i àkukọ ní àárọ̀ yìí
1
yo
Rónmú pariwo ní àárọ̀ yìí
Rónmú se oúnjẹ
Rónmú ti lọ ra àkukọ lọ́ja ní àárọ̀ yìí
0
yo
Mo fẹ́ jẹ ẹ̀bà àti ọbẹ
Ọbẹ̀ àti ẹ̀bà nàá korò
Ojú ọbẹ̀ àti ẹ̀bà tí ó sè ń pe àwọn aràn inú mi
0
yo
Mo fẹ́ jẹ ẹ̀bà àti ọbẹ
Ọbẹ̀ àti ẹ̀bà nàá korò
Ojú ọbẹ̀ àti ẹ̀bà tí ó sè rí bí i ẹrọ̀fọ̀
1
yo
Ebi ń pamí gidigan
Mo ti fún ebi níṣẹ́
Ebi ti fẹ́ kó ìfun mi lé mi lọ́wọ́ nígbà tí mo jí
1
yo
Ebi ń pamí gidigan
Mo ti fún ebi níṣẹ́
Ebi kò pa mí mo ti jẹun yó
0
yo
Ajá Tifẹ́ lé mi léré
Ajá Tifẹ́ jẹ egungun
Ajá Tifẹ́ gba bàtà lẹ́sẹ̀ mi, ẹ̀sẹ̀ mi ò balẹ̀
1
yo
Ajá Tifẹ́ lé mi léré
Ajá Tifẹ́ jẹ egungun
Mo fẹ́ràn láti ma bá ajá Tifẹ́ ṣerẹ́
0
yo
Lọ́ládé bínú sí ọ̀rọ̀ náà
Lọ́ládé rẹ́rìn-ín sí ọ̀rọ̀ náà
Lọ́ládé gbé ọ̀rọ̀ náà sórí bí i igbá ọtí
1
yo
Lọ́ládé bínú sí ọ̀rọ̀ náà
Lọ́ládé rẹ́rìn-ín sí ọ̀rọ̀ náà
Lọ́ládé ti sọ ọ̀rọ̀ kóríyá fún àwọn akẹ́kọ̀ó
0
yo
Àwọn irúgbìn oko yìí nílò omi
Awọn irúgbìn oko yìí ti sùn
Àwọn irúgbìn oko yìí ń sunkún fún omi
1
yo
Àwọn irúgbìn oko yìí nílò omi
Awọn irúgbìn oko yìí ti sùn
Òjò ti rọ̀ sí orí àwọn irúgbìn oko náà
0
yo
Àwọn ìbejì náà sunkún gan
Àwọn ìbejì náà lọ sí ọjà
Àwọn ìbejì náà sun ẹ̀jẹ̀ nígbà tí bàbá àgbà kú
1
yo
Àwọn ìbejì náà sunkún gan
Àwọn ìbejì náà lọ sí ọjà
Àwọn ìbejì náà má ń fi irùngbọ̀n bàbá wọn ṣeré
0
yo
Ìyá àgbà pẹ́ kọ́ tó wọ bàtà tán
Ìyá àgbà ò wọ bàtà tán
Ogún ọdún ni ìyá àgbà lò kọ́ tó wọ bàtà tán
0
yo
Ìyá àgbà pẹ́ kọ́ tó wọ bàtà tán
Ìyá àgbà ò wọ bàtà tán
ìṣéjú kan ni ìyá àgbà lò láti fi wọ bàtà
1
yo
Mo lè sùn fún ìgbà pípẹ́
Mo lè sùn fún wákàtí kan
Ó ti rẹ̀mí mo lè sùn fún ọdún mẹ́ta
0
yo
Mo lè sùn fún ìgbà pípẹ́
Mo lè sùn fún wákàtí kan
Ó ti rẹ̀mí mo lè̀ gbé májèlé jẹ
1
yo
Àlàmú wọlé láì pariwo lánàá
Àlàmú gan ẹsẹ̀ mọ́lẹ̀ wọlé lánàá
Àlàmú wọlé bí i òlè lórú lánàá nígbà tí a ti sùn
0
yo
Àlàmú wọlé láì pariwo lánàá
Àlàmú gan ẹsẹ̀ mọ́lẹ̀ wọlé lánàá
Àlàmú fọ́ gbogbo ilẹ̀kùn ilé kó tó wọlé
1
yo
Bàba Ṣẹ́gun pá lórí
Irun orí bàba Ṣẹ́gun kún gan
Irun orí bàba Ṣẹ́gun jájẹ láàárín orí bí i irun orí báálẹ̀ agboolé Ṣétù
1
yo
Bàba Ṣẹ́gun pá lórí
Irun orí bàba Ṣẹ́gun kún gan
Bàba Ṣẹ́gun ti di báálẹ̀ agboolé Ṣétù
0
yo
Ó ní àǹfàní púpọ̀
Àǹfàní rẹ̀ mẹ́hẹ
Ọ̀pọ̀lọpọ̀ àǹfàní ló ń kan ìlẹ̀kùn ilé rẹ
0
yo
Ó ní àǹfàní púpọ̀
Àǹfàní rẹ̀ mẹ́hẹ
Ọ̀pọ̀lọpọ̀ àǹfàní ló ti tilẹ̀kùn mọ́
1
yo
Ètè rẹ̀ tóbi
Ètè rẹ̀ kéré
Elétè ṣípotì bí i ètè ràkúnmí
1
yo
Ètè rẹ̀ tóbi
Ètè rẹ̀ kéré
Ètè ràkúnmí tí wọ́n se fún mi jẹ̀ dùn gan
0
yo
Ẹniafẹ́ rẹ́rìn-ín gan
Ẹniafẹ́ fojúro
Ẹniafẹ́ rẹ́rìn-ín bí i ẹni tó ní gángàngán
1
yo
Ẹniafẹ́ rẹ́rìn-ín gan
Ẹniafẹ́ fojúro
Ẹniafẹ́ fi rẹ́rìn-ín gba owó lọ́wọ bàbá rẹ̀.
0
yo
Mo fẹ́ lọ yàgbẹ́
Mo fẹ́ lọ jẹun
Mo fẹ́ lọ ṣe ìgbọ̀nsẹ̀ níwájú ilé ìjosìn wa
1
yo
Mo fẹ́ lọ yàgbẹ́
Mo fẹ́ lọ jẹun
Mo fẹ́ lọ gbàdúra níwájú ilé ìjosìn wa
0
yo
Àjọ àgbáyé ti yọ ààrẹ Bùhárí kúrò lórí oyè
Àjọ àgbáyé ti fún ààrẹ Bùhárí níṣẹ́ tuntun
Àwọn ajọ àgbáyé ti júwe ọ̀na ilé fún ààrẹ Bùhárí nítorí àìṣe ìtọ́jú àwọn ará ìlú
1
yo
Àjọ àgbáyé ti yọ ààrẹ Bùhárí kúrò lórí oyè
Àjọ àgbáyé ti fún ààrẹ Bùhárí níṣẹ́ tuntun
Àwọn ajọ àgbáyé ti fún ààrẹ Bùhárí lóyè tuntun
0
yo
Tanitolúwa jẹ́ ẹni tó dángájíá níbi ìṣètò ìlú
Tanitolúwa jẹ́ aláìmọ̀kan níbi ìṣètò ìlú
Tanitolúwa jẹ́ ẹni tó fi gbọ̀ọ̀rọ̀ jẹkà níbi ká ṣètò ìlú
0
yo
Tanitolúwa jẹ́ ẹni tó dángájíá níbi ìṣètò ìlú
Tanitolúwa jẹ́ aláìmọ̀kan níbi ìṣètò ìlú
Tanitolúwa ò lè fi gbọ̀ọ̀rọ̀ jẹkà níbi ká ṣètò ìlú
1
yo
Ẹniọlá àti àwọn ọ̀rẹ́ rẹ̀ kọ̀ mọ ǹkankan
Ẹniọlá àti àwọn ọ̀rẹ́ rẹ̀ mọ ìwé gan
Àgbá òfìfo ni orí Ẹniọlá àti àwọn ọ̀rẹ́ rẹ̀
1
yo
Ẹniọlá àti àwọn ọ̀rẹ́ rẹ̀ kọ̀ mọ ǹkankan
Ẹniọlá àti àwọn ọ̀rẹ́ rẹ̀ mọ ìwé gan
Orí Ẹniọlá àti àwọn ọ̀rẹ́ rẹ̀ ti pé jù
0
yo
Àwọn ará ìlú ti rí ààrẹ Bùhárí fín gan
Àwọn ará ìlú máa ń bọ̀wọ̀ fún ààrẹ Bùhárí
Gbogbo ará ìlú ti sọ ààrẹ Bùhárí di igbá ìkólẹ̀
1
yo
Àwọn ará ìlú ti rí ààrẹ Bùhárí fín gan
Àwọn ará ìlú máa ń bọ̀wọ̀ fún ààrẹ Bùhárí
Gbogbo ará ìlú nífẹ̀ẹ́ ààrẹ Bùhárí
0
yo
Wọ́n ti dá olùkọ́ dúró lẹ́nu iṣẹ́
Wọ́ fún olùkọ́ wa ní ìgbéga lẹ́nu iṣẹ́
Ilé ẹ̀kọ́ fásitì ti pàṣẹ lọ rọọ́kún sílé fún olùkọ́ wa tó fipá bá akẹ́kọ̀ọ́ lò pọ̀
1
yo
Wọ́n ti dá olùkọ́ dúró lẹ́nu iṣẹ́
Wọ́ fún olùkọ́ wa ní ìgbéga lẹ́nu iṣẹ́
Ilé ẹ̀kọ́ fásitì ti ṣe àfikún sí owó oṣù àwọn olùkọ́ wa
0
yo
Ojú abẹ́ Dérìnọlá ti jìn gan
Ojú abẹ́ Dérìnọlá dùn
Ojú abẹ́ Dérìnọlá ti gìn bí i kọ̀ǹga
1
yo
Ojú abẹ́ Dérìnọlá ti jìn gan
Ojú abẹ́ Dérìnọlá dùn
Ojú abẹ́ Dérìnọlá dà bí i ti wúndíá
0
yo
Èrò pọ̀ gan lọ́jọ́ ìkómọ Àdìó
Àwọn ènìyàn kọ̀ wá
Lọ́jọ́ ìkómọ Àlàó pẹ́pẹ́yẹ kọmọ
0
yo
Èrò pọ̀ gan lọ́jọ́ ìkómọ Àdìó
Àwọn ènìyàn kọ̀ wá
Lọ́jọ́ ìkómọ Àlàó dà bí i aṣálẹ̀
1
yo
Óunjẹ pọ̀ gan níbi ìnáwó oyè jíjẹ tí mo lọ
Óunjẹ tí mo jẹ níbi ìnáwó oyè jíjẹ kò tó rárá
Níbi ìnáwó oyè jíjẹ tí mo lọ, wọ́n filé pọtí, wọ́n fọ̀nà rokà, wọ́n fí gbogbo agbada díran
0
yo
Óunjẹ pọ̀ gan níbi ìnáwó oyè jíjẹ tí mo lọ
Óunjẹ tí mo jẹ níbi ìnáwó oyè jíjẹ kò tó rárá
Níbi ìnáwó oyè jíjẹ tí mo lọ, mo ò rí nǹkankan fẹnu gbá
1
yo
Ladé ti wọ wàhálà ìjọba
Ladé àti ìjọbá rẹ́
Ladé ti kẹ́ran lọ́wọ́ ìjọba
1
yo
Ladé ti wọ wàhálà ìjọba
Ladé àti ìjọbá rẹ́
Ladé ti ń bá ìjọba ṣiṣẹ́
0
yo
Àdìgún ti ń jalè
Àdìgún ti ra bàtà tuntun
Àdìgún ti ń fẹ́wọ́ láti kékeré
1
yo
Àdìgún ti ń jalè
Àdìgún ti ra bàtà tuntun
Àdìgún ti lawọ́ láti kékeré
0
yo
Nígbà tí oòrùn ràn gidi gan ni kábíyèsí ránṣẹ́ pè mí
Nígbà tí oòrùn wọ̀ ni mo jáde
Nígbà tí déédé oòrùn kan àtàrí ni kábíyèsí ránṣẹ́ pè mí
0
yo
Nígbà tí oòrùn ràn gidi gan ni kábíyèsí ránṣẹ́ pè mí
Nígbà tí oòrùn wọ̀ ni mo jáde
Nígbà tí àwọn ọmọ náà bẹ̀rẹ̀ sí ní jà ni kábíyèsí ránṣẹ́ pè mí
1
yo
Ó ń rìn kiri
Ó ń jókòó pawó
Ó ń fi ẹ̀sẹ̀ gbá gbogbo ìgboro kiri
1
yo
Ó ń rìn kiri
Ó ń jókòó pawó
Ó ń fi gègé kọ ìwé owó kiri
0
yo
Kò sí ọ̀nà rárá láti gbà
Ọkọ̀ tó pọ̀ ló wà lójú ọ̀nà
Ojú ọ̀nà náà dí pákópákó bí i ọjú ọ̀nà Ìsọlọ̀ sí Ìjẹgun
1
yo
Kò sí ọ̀nà rárá láti gbà
Ọkọ̀ tó pọ̀ ló wà lójú ọ̀nà
Mo ti ra ilé tuntun sí ọjú ọ̀nà Ìsọlọ̀ sí Ìjẹgun
0
yo
Bọ́lájí mọ iṣẹ́ igbá fínfín dáadáa
Ìmọ̀ Bọ́lájí kò ì tó nípa igbá fínfín
Ìmọ̀ Bọ́lájí kún nípa iṣẹ́ igbá fínfín bí i àwọn ará Ọ̀yọ́
0
yo
Bọ́lájí mọ iṣẹ́ igbá fínfín dáadáa
Ìmọ̀ Bọ́lájí kò ì tó nípa igbá fínfín
Ìmọ̀ Bọ́lájí kò tí ì kún nípa iṣẹ́ igbá fínfín
1
yo
Omi gàrí náà kan gan
Omi gàrí náà ta lẹ́nu
Omi gàrí tí mo mu lánàá kan bí i omi ògì
0
yo
Omi gàrí náà kan gan
Omi gàrí náà ta lẹ́nu
Omi gàrí tí mo mu lánàá korò bí i àgbo
1
yo
Délaní mọ ọfà ta dáadáa
Délaní ò rí ẹyẹ pa
Délaní mọ ọfà ta bí i àwọn ògbójú ọdẹ tafàtafà
0
yo
Délaní mọ ọfà ta dáadáa
Délaní ò rí ẹyẹ pa
Délaní ò mọ ọfà ta bí i àwọn ògbójú ọdẹ
1
yo
Mo ma ṣe àṣeyọ́ri nínú ẹ̀kọ́ mi àti nínú iṣẹ́ mi
Mo ma ṣe iṣẹ́ díẹ̀ nínú ẹ̀kọ́ ní ọ̀la
Mo ma dé òkè tó ga jùlọ nínú ẹ̀kọ́ mi àti nínú iṣẹ́ mi
0
yo
Mo ma ṣe àṣeyọ́ri nínú ẹ̀kọ́ mi àti nínú iṣẹ́ mi
Mo ma ṣe iṣẹ́ díẹ̀ nínú ẹ̀kọ́ ní ọ̀la
Ọmọ náà ò dé òkè tó ga jùlọ nínú ẹ̀kọ́ rẹ̀
1
yo
Àbíkú l'àwọn ọmọ tó ń bí
Ìbejì l'àwọn ọmọ tí mo bí
Aládòó-òfo ni àwọn ọmọ tó ń bí
1
yo
Àbíkú l'àwọn ọmọ tó ń bí
Ìbejì l'àwọn ọmọ tí mo bí
Àwọn ọmọ tó ń bí ò kì í ṣe aládòó-òfo
0
yo
Àbẹ̀bí sáré jáde lọ gbé ọmọ rẹ̀
Àbẹ̀bí ń wọ́ tìkọ̀tìkọ̀ lọ gbé ọmọ rẹ̀
Àbẹ̀bí já ṣòròrò jáde lọ gbé ọmọ rẹ̀ tó fẹ́ já sínú kọ̀ǹga
0
yo
Àbẹ̀bí sáré jáde lọ gbé ọmọ rẹ̀
Àbẹ̀bí ń wọ́ tìkọ̀tìkọ̀ lọ gbé ọmọ rẹ̀
Ọmọ Àbẹ̀bí ti kú sínú kọ̀ǹga
1
yo
Kò pọn ọmọ náà dáadáa
Ó pọn ọmọ mẹ́fà papọ̀
Ó pọn ọmọ bí i ẹni tí Elédùnmarè ò kọmọ mọ́
1
yo
Kò pọn ọmọ náà dáadáa
Ó pọn ọmọ mẹ́fà papọ̀
Ó pọn ọmọ bí i ẹni tí Elédùnmarè ò kọmọ mọ́
0
yo
Jíbíkẹ̀ẹ́ mọ bí wọ́n ṣé ń yí ìbàdí fún àwọn ọkùnrin
Ìbàdí Jíbíkẹ̀é ti gan
Ẹ wo bí Jíbíkẹ̀ẹ́ ṣe ń ṣe ìbàdí rẹ̀ fún àwọn ọkùnrin bí i ọmọrí odó tí wọ́n yí kiri
0
yo
Jíbíkẹ̀ẹ́ mọ bí wọ́n ṣé ń yí ìbàdí fún àwọn ọkùnrin
Ìbàdí Jíbíkẹ̀é ti gan
Ìranù ni Jíbíkẹ̀ẹ́ ṣe pẹ̀lú àwọn ọkùnrin
1
yo
Iyán tí Ṣadé sè ti tutù gan
Iyán tí Ṣadé sè ń yọ eruku lálá
Iyán ti Ṣadé sè ti tutù bí i imú ajá nígbà tí mo fẹ́ jẹun
0
yo
Iyán tí Ṣadé sè ti tutù gan
Iyán tí Ṣadé sè ń yọ eruku lálá
Iyán ti Ṣadé sè ti bàjẹ́
1
yo
Bọ́lájókòó ò ṣe ohun tí adájọ́ sọ fún nílé ẹjọ́
Adájọ́ fi Bọ́lájókòó sẹ́wọ̀n lánàá
Bọ́lájókòó kọtí ọ̀gbọ̀n-in sẹ́bọ lóri ohun tí adájọ́ sọ fun nílé ẹjọ́
1
yo
Bọ́lájókòó ò ṣe ohun tí adájọ́ sọ fún nílé ẹjọ́
Adájọ́ fi Bọ́lájókòó sẹ́wọ̀n lánàá
Bọ́lájókòó rú ẹ́bọ ayé rẹ̀ si da
0
yo
Ebi ṣì ń pamí, mo ò tí ì yó
Inú mi ti kún bákán
Èmi pàápàá gan ò tí i jẹun yó bátákú bí i ìdun tó ń wọ́ rìn kí ń tó kúro nílé
1
yo
Ebi ṣì ń pamí, mo ò tí ì yó
Inú mi ti kún bákán
Èmi pàápàá gan tí i jẹun yó bátákú
0
yo
Olùjẹ́jọ́ ti ṣi ọ̀rọ̀ sọ fún adájọ́
Olùjẹ́jọ́ ti gbé adájọ́ lọ ilé ẹjọ́
Olùjẹ́jọ́ ti gbọ́mọ ọbà f'ọ́ṣun nígbà tí ó ń ṣàlàyè ọ̀rọ̀ fún adájọ́
0
yo
Olùjẹ́jọ́ ti ṣi ọ̀rọ̀ sọ fún adájọ́
Olùjẹ́jọ́ ti gbé adájọ́ lọ ilé ẹjọ́
Olùjẹ́jọ́ ti sọ ọ̀rọ̀ àìda sí adájọ́
1
yo
Bàbá Déòtí ti kú
Bàbá Déòtí lọ ṣe ìpàdé lọ́dọ̀ àwọn àgbàgbà ìlú
Bàbá Déòtí ti rebi àgbà ń rè ní ìdájí òní
1
yo
Bàbá Déòtí ti kú
Bàbá Déòtí lọ ṣe ìpàdé lọ́dọ̀ àwọn àgbàgbà ìlú
Bàbá Déòtí ti rebi tó ti fẹ́ joyè
0
yo
O tí pẹ́ gan ti mo mu irú ẹmu ògùrọ̀ yìí
Ẹmu tí mo mu ò dára
Mo ti mu irú ẹmu ògùrọ̀ báyìí ilẹ̀ ta sí i
0
yo
O tí pẹ́ gan ti mo mu irú ẹmu ògùrọ̀ yìí
Ẹmu tí mo mu ò dára
Irú ẹmu ògùrọ̀ ti mo yìí ò dùn rárá
1
yo
Bádégún ṣe ìpàdé ẹgbẹ́ dáadáa, ọ̀pọ̀ jíjẹ àti mímu ló wà
Kò sí àwọn àgbàgbà níbi ìpàdé ẹgbẹ́ tí Bádégún ṣe
Bádégún ṣe ìpàdé ẹgbẹ́ lánàá bí i ẹní ṣe ìnáwó oyè jíjẹ
0
yo
Bádégún ṣe ìpàdé ẹgbẹ́ dáadáa, ọ̀pọ̀ jíjẹ àti mímu ló wà
Kò sí àwọn àgbàgbà níbi ìpàdé ẹgbẹ́ tí Bádégún ṣe
Bádégún ò nífẹ̀ẹ́ sí kí àwọn àgbàgbà wá síbi ìpàdé ẹgbẹ́ rẹ̀
1
yo
Alájẹ jù ni àwọn tọ́ wá sí ibi ìnáwó wa lánàá
Àwọn tọ́ wá sí ibi ìnáwó wa lánàá wọn ò rí óunjẹ jẹ
Alájẹ fẹnu nulẹ̀ bí i adìẹ ni àwọn tó wá sí ibi ìnáwó wa lánàá
1
yo
Alájẹ jù ni àwọn tọ́ wá sí ibi ìnáwó wa lánàá
Àwọn tọ́ wá sí ibi ìnáwó wa lánàá wọn ò rí óunjẹ jẹ
Alájẹ fẹnu pamọ́ ni àwọn tó wá sí ibi ìnáwó wa lánàá
0
yo
Báyọ̀ ò sanwó oúnjẹ lẹ́yìn tó jẹun tan
Báyọ̀ kó owó gọbọi wá sílé oúnjẹ lánàá
Báyọ̀ gbọ̀ndí gbùú lẹ́yìn tó jẹun tan kò gbọnwọ́ nǹkankan sáwo fún ẹni tó ta oúnjẹ fun
1
yo
Báyọ̀ ò sanwó oúnjẹ lẹ́yìn tó jẹun tan
Báyọ̀ kó owó gọbọi wá sílé oúnjẹ lánàá
Báyọ̀ gbọnwọ́ sáwo lẹ́yìn tó jẹun tan
0
yo
Àwọn èrònjà èkuru ti ṣòro láti rírà lọ́jà
Wọ́n kó àwọn èrònjà èkuru dé ọjà
Àwọn èrònjà ta fí ń se èkuru ti di imí eégún lọ́jà
1
yo
Àwọn èrònjà èkuru ti ṣòro láti rírà lọ́jà
Wọ́n kó àwọn èrònjà èkuru dé ọjà
Àwọn èrònjà ta fí ń se èkuru ti pọ̀jù lọ́jà
0
yo
Alóńgẹ́ mọ irọ́ pa gan
Alóńgẹ́ kì í pa irọ́
Alóńgẹ́ ti so iró di ọkà tó ń jẹ pẹ̀lú ọbẹ̀ ìṣápá
0
yo
Alóńgẹ́ mọ irọ́ pa gan
Alóńgẹ́ kì í pa irọ́
Alóńgẹ́ ti so iró nàá di òótọ́ mọ́ wa lọ́wọ́
1
yo