ending1
stringlengths
4
149
ending2
stringlengths
5
156
startphrase
stringlengths
7
179
labels
int64
0
1
split
stringclasses
7 values
Bọ́lájókòó ń fi ọ̀pá rìn
Bọ́lájókòó ń fi ọ̀pá ṣeré
Ẹsẹ̀ mẹ́ta ni Bọ́lájókòó fi ń rin bí i àwọn atọrọbáárà
0
yo
Bọ́lájókòó ń fi ọ̀pá rìn
Bọ́lájókòó ń fi ọ̀pá ṣeré
Ẹsẹ̀ tó ti kán ni Bọ́lájókòó fi ń rin
1
yo
Iyán náà rọ̀
Iyán náà le
Iyán náà fẹ́lẹ́ bí i etí
0
yo
Iyán náà rọ̀
Iyán náà le
Iyán náà wúwo bí i òkúta
1
yo
Ìdánwò náà gbomi mu
Ìdánwò náà rọrùn
Ìdí àwọn akẹ́kọ̀ọ́ yọ eruku lala bí i omi gbóná nínú yàrá ìdánwò
0
yo
Ìdánwò náà gbomi mu
Ìdánwò náà rọrùn
Àwọn akẹ́kọ̀ọ́ sùn fọnfọn nínú yàrá ìdánwò
1
yo
Adé́gbètẹ̀ bínú nígbà tí ó ń bá ọ̀rẹ́ rẹ̀ sọ̀rò
Adé́gbètẹ̀ rẹ́rìn ín nígbà tí ó ń bá ọ̀rẹ́ rẹ̀ sọ̀rò
Adégbètẹ́ tu itọ́ sókè fojú gbáà nígbà tí ó ń bá ọ̀rẹ́ Mákindé sòrò
0
yo
Adé́gbètẹ̀ bínú nígbà tí ó ń bá ọ̀rẹ́ rẹ̀ sọ̀rò
Adé́gbètẹ̀ rẹ́rìn ín nígbà tí ó ń bá ọ̀rẹ́ rẹ̀ sọ̀rò
Adégbètẹ́ bú sẹ́kún nígbà tí ó ń bá ọ̀rẹ́ Mákindé sòrò
1
yo
Arákùnrin ná́à ti kú
Arákùnrin ná́à wá ọ̀nà àbáyọ
Arákunrìn náà ta téru nípàá níbi ìṣẹ̀lẹ̀ ìjàmbá ọkọ̀
1
yo
Arákùnrin ná́à ti kú
Arákùnrin ná́à wá ọ̀nà àbáyọ
Arákunrìn náà ra ọkọ̀ tuntun
0
yo
Ẹ̀gbọ́n Símisọ́lá ò ga
Ẹ̀gbọ́n Símisọ́lá sùn lọ
Ẹ̀gbọ́n Símisọ́lá rí bí i Àdìgún tí kò yọ kúrò nílẹ̀
1
yo
Ẹ̀gbọ́n Símisọ́lá ò ga
Ẹ̀gbọ́n Símisọ́lá sùn lọ
Ẹ̀gbọ́n Símisọ́lá ti fẹ́ àbúrò Àdìgún tó rẹwà
0
yo
Èésúọlá àti àwọn ọ̀rẹ́ rẹ̀ ń jà
Èésúọlá àti àwọn ọ̀rẹ́ rẹ̀ ṣeré kiri
Èésúọlá àti àwọn ọ̀rẹ́ rẹ̀ yóò kẹsẹ̀ bọ sòkòtò kan ná-àn, ọlọ́pàá sì kó wọn
1
yo
Èésúọlá àti àwọn ọ̀rẹ́ rẹ̀ ń jà
Èésúọlá àti àwọn ọ̀rẹ́ rẹ̀ ṣeré kiri
Èésúọlá àti àwọn ọ̀rẹ́ rẹ̀ yóò aṣọ tó rẹwà tó sì jọra
0
yo
Ilé awòṣífìnà náà rẹwà
Ilé awòṣífìnà náà ti wó
Ilé awòṣífìlà tó kọ́ rí bí i ààfin Ọba Ọọ̀ni ilé Ifẹ̀
0
yo
Ilé awòṣífìnà náà rẹwà
Ilé awòṣífìnà náà ti wó
Ilé awòṣífìlà tó kọ́ ti wó lul̀e
1
yo
O tí dàgbà gan
O kéré gan
Ọjọ́ orí rẹ̀ ju ọjọ́ ori ij̀àpá lọ
0
yo
O tí dàgbà gan
O kéré gan
Ọjọ́ orí rẹ̀ kò tó ọjọ́ ori ij̀àpá lọ
1
yo
Àdìsá mu ẹmu púpọ̀
Àdìsá mu ẹmu kekeré
Àdìsà mu kòkò ẹmu ọgbọ̀n ní ilé ẹmu lánàá
0
yo
Àdìsá mu ẹmu púpọ̀
Àdìsá mu ẹmu kekeré
Àdìsà kò mu ẹmu rárá ní ilé ẹmu lánàá
1
yo
Ọdẹ́ṣọlá mọ iṣẹ́ ọdẹ náà dáadáa
Ọdẹ́ṣọlá ń fi iṣẹ́ ọdẹ ṣeré
Ọdẹ́ṣọlá ní òye iṣẹ́ ọdẹ náà dójú àmì bí i olúọ́dẹ agboolé wa
0
yo
Ọdẹ́ṣọlá mọ iṣẹ́ ọdẹ náà dáadáa
Ọdẹ́ṣọlá ń fi iṣẹ́ ọdẹ ṣeré
Ọdẹ́ṣọlá ò mọ iṣẹ́ tí wọ́n pè ni iṣẹ́ ọdẹ.
1
yo
Díẹ̀ díẹ̀ ló ń gba owó rẹ̀ padà
Ó ṣe ìtọrẹ àánú pẹ̀lú owó rẹ̀
Ení tere èji tere ló ń gba owó rẹ̀ padà bí i àwọn alájẹṣẹ́ku
0
yo
Díẹ̀ díẹ̀ ló ń gba owó rẹ̀ padà
Ó ṣe ìtọrẹ àánú pẹ̀lú owó rẹ̀
Ení tere èji tere kọ́ ló gba owó rẹ̀ padà
1
yo
Agbẹjọ́rò náà ti sọ àṣírí ọ̀rọ̀ náà
Agbẹjọ́rò náà ti sú ìgbẹ́jọ́ náà
Agbẹjọ́rò náà ti ṣíṣọ lójú eégún ọ̀rọ̀ náà nílé ẹjọ́
0
yo
Agbẹjọ́rò náà ti sọ àṣírí ọ̀rọ̀ náà
Agbẹjọ́rò náà ti sú ìgbẹ́jọ́ náà
Agbẹjọ́rò náà ò sọ ẹni tó jẹ̀bi
1
yo
Àwọn ènìyàn púpọ̀ wà lọ́jà
Àwọn mẹ́ta péré ló wà lọ́jà
Èrò tó wà lọ́jà kún àkúnfàya lánàá
0
yo
Àwọn ènìyàn púpọ̀ wà lọ́jà
Àwọn mẹ́ta péré ló wà lọ́jà
Àwọ́n èrò tó wà lọ́jà tí fi ọlọ́pàá gbé bàbá ọjà lánàá
1
yo
Fadékẹ́ ti padà dárjíì mìí
Fadékẹ́ ti padà bínú sí mi
Inú Fadékẹ́ ti padà yọ́ sí mi bí i òrí lánàá lẹ́yìn gbogbo ìjà wa
0
yo
Fadékẹ́ ti padà dárjíì mìí
Fadékẹ́ ti padà bínú sí mi
Fadékẹ́ ti padà bí ìbejì lẹ́yìn gbogbo ìjà wa
1
yo
Eréepá ni àwọn ọmọ náà ṣe kiri
Àwọn ọmọ náà jókòó sí ibìkan
Ìka kan ò wọ àwọn ọmọ yìí nídìí mọ́
0
yo
Eréepá ni àwọn ọmọ náà ṣe kiri
Àwọn ọmọ náà jókòó sí ibìkan
À̀wọn ọmọ yìí ti lọ sóko ọ̀gẹ̀dẹ̀
1
yo
Wọ́n dájọ́ ẹ̀wọ̀n ọdún mọ́kànlá fun nílé ẹjọ́
Ó ń polówó ọjà nílé ẹjọ́
Ó rí ẹ̀wọ̀n ọdún mọ́kànlá he nílé ẹjọ́ lóri ẹ̀sùn tí wọ́n fi kàn-án
1
yo
Wọ́n dájọ́ ẹ̀wọ̀n ọdún mọ́kànlá fun nílé ẹjọ́
Ó ń polówó ọjà nílé ẹjọ́
Lẹ́yìn ẹ̀wọ̀n ọdún mọ́kànlá tó rí he ó padà gba ìtúsílẹ̀
0
yo
Adénúgà pọ́n igi gùn dáadáa
Adénúgà sùn lóri igi
Ẹ wo bí Adénúgà ṣe ń gun igi bí i ọ̀bọ
1
yo
Adénúgà pọ́n igi gùn dáadáa
Adénúgà sùn lóri igi
Adénúgà nífẹ̀ẹ́ sí bí àwọn ọ̀bọ ṣé n gun igi
0
yo
Tifẹ́ladé máa ń sọ àsọdùn ọ̀rọ̀
Tifẹ́ladé kì í sòrò
Ẹnu ni Tifẹ́ladé ni bí i tajakàrà
0
yo
Tifẹ́ladé máa ń sọ àsọdùn ọ̀rọ̀
Tifẹ́ladé kì í sòrò
Tifẹ́ladé kò mọ̀ bi wọ́n ṣe dan ẹnu
1
yo
Ìwà ọmọdé ni Adéṣínà máa ń wù
Adéṣínà nífẹ̀ẹ́ sí kó ma tọ̀ sára
Kí ló dé tí Adéṣínà ṣe máa ń hùwà bí i atọ̀ọ́lé?
1
yo
Ìwà ọmọdé ni Adéṣínà máa ń wù
Adéṣínà nífẹ̀ẹ́ sí kó ma tọ̀ sára
Kí ló dé tí Adéṣínà ṣe ra ilé tuntun?
0
yo
Àlàó kò kúrò lójú kan
Àlàó ń rìn kiri
Ẹ wo bí Àlàó ṣe duró bí i omi adágún odò
1
yo
Àlàó kò kúrò lójú kan
Àlàó ń rìn kiri
Ẹ wo bí Àlàó ṣe duró bí i Ọba
0
yo
Àwọn olè náà sálọ
Àwọn olè náà gbé ìbọn wọn jáde
Àwọn olè náà júbà eworo nígbà tí wọ́n gbúròó àwọn ọlọ́pàá
0
yo
Àwọn olè náà sálọ
Àwọn olè náà gbé ìbọn wọn jáde
Àwọn olè náà yin ìbọn nígbà tí wọ́n gbúròó àwọn ̀ọlọ́pàá
1
yo
Ó ti pẹ́ gan tí Wọléọlá ti wà nínú yàrá
Wọléọlá ṣẹ̀ṣẹ̀ wọ inú yàrá
Ọ̀sẹ̀ kan rèé tí Wọléọlá ti wà nínú yàrá bí i ẹni tọ́ fi s'ẹ́wọ̀n
1
yo
Ó ti pẹ́ gan tí Wọléọlá ti wà nínú yàrá
Wọléọlá ṣẹ̀ṣẹ̀ wọ inú yàrá
Ọ̀sẹ̀ kan rèé tí Wọléọlá ti lọ sí ìlú ọba
0
yo
Ọdẹ́wùnmí kò kí àwọn àgbà ọdẹ dáadáa
Ọdẹ́wùnmí pariwo mọ́ àwọn àgbà ọdẹ
Ọdẹ́wùnmí júbà gbogbo àwọn àgbà ọdẹ bí i ẹni tí kò kọ́ṣẹ́ ọdẹ
0
yo
Ọdẹ́wùnmí kò kí àwọn àgbà ọdẹ dáadáa
Ọdẹ́wùnmí pariwo mọ́ àwọn àgbà ọdẹ
Ọdẹ́wùnmí bú gbogbo àwọn àgbà ọdẹ tí wọn jókòó
1
yo
Adénifújà kì í ṣe ọmọ ẹgbẹ́ wa
Olórí ẹgbẹ́ wa ni Adénifújà
Ọ̀gbẹ̀rì ni Adénifújà nínú ẹgbẹ́ wa
0
yo
Adénifújà kì í ṣe ọmọ ẹgbẹ́ wa
Olórí ẹgbẹ́ wa ni Adénifújà
Adénifújà kì í ṣe Ọ̀gbẹ̀ri nínú ẹgbẹ́ wa
1
yo
Wọ́n na Bọ́lájí gan
Wọ́n gbé Bọ́lájí lọ jayé
Wọ́n na Bólájí nílù bààrà bí i ẹni tó jalè
1
yo
Wọ́n na Bọ́lájí gan
Wọ́n gbé Bọ́lájí lọ jayé
Wọ́n gbé oúnjẹ tó dùn fún Bólájí
0
yo
Arákùnrin náà fẹ́ ìyàwó púpọ̀
Ìyàwó kan ṣoṣo ni arákùnrin náà fẹ́
Arákùnrin náà fẹ́ ìyàwọ̀ lọ bìbà bí i ọba Aláàfin
0
yo
Arákùnrin náà fẹ́ ìyàwó púpọ̀
Ìyàwó kan ṣoṣo ni arákùnrin náà fẹ́
Arákùnrin náà fẹ́ burẹ́wà
1
yo
Ènìyàn tó pọ̀ ló wà ní pápá ìṣeré náà
Ènìyàn mẹ́fà páré ló wà ní pápá ìṣeré náà
Ogúnlọ́gọ̀ àwọn ènìyàn ló wà ní pápá ìṣeré tí wọ́n ti fẹ́ gbá bọ́ọ̀lù ikọ̀ Nàìjíríà
0
yo
Ènìyàn tó pọ̀ ló wà ní pápá ìṣeré náà
Ènìyàn mẹ́fà páré ló wà ní pápá ìṣeré náà
Àwọn ènìyàn tó wà ní pápá ìṣeré tí wọ́n ti fẹ́ gbá bọ́ọ̀lù tí ń jà
1
yo
Ikọ̀ Nàìjíríà ṣe dáadáa níbi ìdíje ife ẹ̀yẹ àgbáyé
Ikọ̀ Nàìjíríà hùwà ìbàjẹ́ níbi ìdíje ife ẹ̀yẹ àgbáyé
Àwọn ikọ̀ Nàìjíríà ti fakọyọ níbí ìdíje ife ẹ̀yẹ àgbáyé ju ti àtẹ̀yìn wá lọ
0
yo
Ikọ̀ Nàìjíríà ṣe dáadáa níbi ìdíje ife ẹ̀yẹ àgbáyé
Ikọ̀ Nàìjíríà hùwà ìbàjẹ́ níbi ìdíje ife ẹ̀yẹ àgbáyé
Àwọn ikọ̀ Nàìjíríà ti kó igbá wọlé níbí ìdíje ife ẹ̀yẹ àgbáyé
1
yo
Etí Arínájà tóbi gan
Etí Arínájà kéré gan
Etí Arínájà rí bí i eté eworo
1
yo
Etí Arínájà tóbi gan
Etí Arínájà kéré gan
Etí Arínájà tí gbọ́ ọ̀rọ̀ dáadáa
0
yo
Adérẹ̀mí na Arímọrọ̀ níbi ìjà ìjàkadì lánàá
Adérẹ̀mí ṣeré pẹ̀lú Arímọrọ̀ níbi ìjà ìjàkadì lánàá
Adérẹ̀mí ṣe Arímọrọ̀ bí ọṣẹ́ ṣé ń ṣojú nígbà tí wọ́n ja ìjà ìjàkadi lánàá
1
yo
Adérẹ̀mí na Arímọrọ̀ níbi ìjà ìjàkadì lánàá
Adérẹ̀mí ṣeré pẹ̀lú Arímọrọ̀ níbi ìjà ìjàkadì lánàá
Adérẹ̀mí gbé Arímọrọ̀ lọ jayé ọba lánàá
0
yo
Àrẹ̀mú ti ń nífẹ̀ẹ́ Ọmọ́ṣaléwá
Àrẹ̀mú ti lọ pọn omi fún Ọmọ́ṣaléwá lódò
Àrẹ̀mú ti ń lúwẹ̀ẹ́ nínú odò ìfẹ́ Ọmọ́ṣaléwá
0
yo
Àrẹ̀mú ti ń nífẹ̀ẹ́ Ọmọ́ṣaléwá
Àrẹ̀mú ti lọ pọn omi fún Ọmọ́ṣaléwá lódò
Àrẹ̀mú ò fẹ́ràn láti ma fojú ri Ọmọ́ṣaléwá
1
yo
Bàbá Agbájé mọ ọyùn mu
Bàbá Agbájé mọ oúnjẹ sè
Bàbá Agbájé ń fẹnu fa ọyùn ìyàwò rẹ̀ bí i ọmọ ìkókó tí kò tí ì já lẹ́nu ọyùn
0
yo
Bàbá Agbájé mọ ọyùn mu
Bàbá Agbájé mọ oúnjẹ sè
Bàbá Agbájé kò fẹnu fa ọyùn ìyàwò rẹ̀
1
yo
Iná ọdẹ náà kò mọ́lẹ̀ dáadáa
Iná ọdẹ náà ti kú
Iná ọdẹ náà tàn bí i iná àtùpà tí epo ti fẹ́ tán nínú rẹ̀
1
yo
Iná ọdẹ náà kò mọ́lẹ̀ dáadáa
Iná ọdẹ náà ti kú
Iná ọdẹ náà tàn, ó sì ríran kedere
0
yo
Adéyẹmí bínú láti àárọ̀
Adéyẹmí rẹ́rìn ín láti àárọ̀
Adéyẹmí kanra bí i ajá elégbọn láti àárọ̀
1
yo
Adéyẹmí bínú láti àárọ̀
Adéyẹmí rẹ́rìn ín láti àárọ̀
Adéyẹmí má ń bá àwọn ajá ṣeré
0
yo
Adéṣọlá ní ìmọ̀ ìjìnlẹ̀ nípa àṣà àti ìṣe ilẹ̀ Yorùbá
Adéṣọlá ní orí kuku
Ọmọ ọ̀dọ̀ àgbà ni Adéṣọlá nínú àṣà àti ìṣe ilẹ̀ Yorùbá
0
yo
Adéṣọlá ní ìmọ̀ ìjìnlẹ̀ nípa àṣà àti ìṣe ilẹ̀ Yorùbá
Adéṣọlá ní orí kuku
Ọmọ Ègùn ni Adéṣọlá kò mọ̀ nípa àṣà ilẹ̀ Yorùbá
1
yo
Adésuà bí ọmọ tuntun lánàá
Adésuà na ọmọ tuntun tó bí
Adésuà fọwọ́ osùn pa ògiri gbígbe lánàá nílé ìwòsàn
0
yo
Adésuà bí ọmọ tuntun lánàá
Adésuà na ọmọ tuntun tó bí
Adésuà ti bẹ̀rẹ̀ sí ni ṣe àìsàn lánàá nílé ìwòsàn
1
yo
Ọjọ́ ti obìnrin bá jẹ ọba ni ìlú ma bàjẹ́
Ọjọ́ ti obìnrin bá jẹ ọba ni ìlú yìí ma tòrò
Ọjọ́ tí òbò bá jẹ ọba lorílẹ̀ èdè yìí ni ìlú bàjẹ́
1
yo
Ọjọ́ ti obìnrin bá jẹ ọba ni ìlú ma bàjẹ́
Ọjọ́ ti obìnrin bá jẹ ọba ni ìlú yìí ma tòrò
Ọba orílẹ̀ èdè yìí ti ṣe ohun mánigbàgbé sí ìlú wa
0
yo
Iyàwò Rọ̀gbà sunkún àìrọ́mọ bí nílé ọkọ rẹ̀
Iyàwò Rọ̀gbà dunnú sí àwọn ọmọ tó bí
Iyàwò Rọ̀gbà sunkún àìrípọ̀n nílé ọkọ rẹ̀ lẹ́yìn ìgbéyàwó ọdún mọ́kànlá
1
yo
Iyàwò Rọ̀gbà sunkún àìrọ́mọ bí nílé ọkọ rẹ̀
Iyàwò Rọ̀gbà dunnú sí àwọn ọmọ tó bí
Iyàwò Rọ̀gbà se oúnjẹ aládùn fún ọkọ rẹ̀
0
yo
Ajá náà bí ọkùnrin àti obìnirin
Ajá náà jẹ ọmọ tó bí
Ajá náà bí akọ àti abo bí i àgùntàn tó bímọ láàrọ́ yìí
0
yo
Ajá náà bí ọkùnrin àti obìnirin
Ajá náà jẹ ọmọ tó bí
Ajá náà kò bí akọ àti abo
1
yo
Àdìmúlà ti kú
Àdìmúlà lọ jí èkuru jẹ
Àdìmúlà ti gbà èkuru jẹ lọ́wọ́ ẹbọra
1
yo
Àdìmúlà ti kú
Àdìmúlà lọ jí èkuru jẹ
Àdìmúlà se èkuru fún à̀wọn ẹgbẹ́ rẹ̀
0
yo
Ilé tí bàbá mi kọ́ rẹwà gan
Ilé tí bàbá mi kọ́ ti wó
Ilé àwòdamiẹnu ni ilé tí bàbá mi kọ́
0
yo
Ilé tí bàbá mi kọ́ rẹwà gan
Ilé tí bàbá mi kọ́ ti wó
Ilé àwòdamiẹnu tí bàbá mi kọ́ ti wó
1
yo
Ìjọba pa arákùnrin náà
Ìjọba gbé arákùnrin náà lọ ilé ẹjọ́
Ìjọba yẹgi fún arákùnrin náà tó jí owó ìjọba gbé
1
yo
Ìjọba pa arákùnrin náà
Ìjọba gbé arákùnrin náà lọ ilé ẹjọ́
Ìjọba ti fún arákùnrin náà ní owó tó pọ̀.
0
yo
Àwọn ọ̀rẹ́ mi ti lọ tú àṣírí ohun tí a ṣe lánàá
Àwọn ọ̀rẹ́ mi ti lọ gbé ohun tí a ṣe lánàá
Àwọn ọ̀rẹ́ mi ti lọ gbẹ̀yìn bẹbo jẹ́ lóri ohun tí a ṣe lánàá
1
yo
Àwọn ọ̀rẹ́ mi ti lọ tú àṣírí ohun tí a ṣe lánàá
Àwọn ọ̀rẹ́ mi ti lọ gbé ohun tí a ṣe lánàá
Àwọn ọ̀rẹ́ mi ló ra aṣọ tí mo wọ̀ lánàá
0
yo
Ẹ̀pà tó pọ̀ ni Mojí yan lálẹ́ àná
Ẹ̀pà ni Mojí jẹ lálẹ́ àná
Apo ẹ̀pà ẹgbẹ̀rún mẹ́fà ni Mojí yan lálẹ́ àná kin tó sùn
0
yo
Ẹ̀pà tó pọ̀ ni Mojí yan lálẹ́ àná
Ẹ̀pà ni Mojí jẹ lálẹ́ àná
Ẹ̀pà hóró mẹ́fà ni Mojí yan lálẹ́ àná kin tó sùn
1
yo
Àmọ̀pé rawọ́ ẹ̀bẹ̀ sí Olódùmarè fún gbogbo àwọn tí wọ́n lóyún
Àmọ̀pé rawọ́ ẹ̀bẹ̀ sí Olódùmarè fún gbogbo àwọn ọmọdé
Àmọ̀pé rawọ́ ẹ̀bẹ̀ sí Olódùmarè fún gbogbo àwọn tí wọ́n diwọ́ disẹ̀ sínú
0
yo
Àmọ̀pé rawọ́ ẹ̀bẹ̀ sí Olódùmarè fún gbogbo àwọn tí wọ́n lóyún
Àmọ̀pé rawọ́ ẹ̀bẹ̀ sí Olódùmarè fún gbogbo àwọn ọmọdé
Àmọ̀pé ṣépè fún gbogbo àwọn tí wọ́n diwọ́ disẹ̀ sínú
1
yo
Ọ̀kẹ́ ṣiṣẹ́ láì sinmi
Ọ̀kẹ́ ṣiṣẹ́ ọpọlọ
Ọ̀kẹ́ ṣiṣẹ́ bí i omi òjò lánàá
0
yo
Ọ̀kẹ́ ṣiṣẹ́ láì sinmi
Ọ̀kẹ́ ṣiṣẹ́ ọpọlọ
Ọ̀kẹ́ ò ṣiṣẹ́ kankan rárá lánàá
1
yo
Bàbá Àgbà ti kú
Bàbá Àgbà ti wo aṣọ tuntun
Bàbá àgbà tẹ́rígbaṣọ lẹ́yìn ìnáwó tí a ṣe lánàá
0
yo
Bàbá Àgbà ti kú
Bàbá Àgbà ti wo aṣọ tuntun
Bàbá àgbà raṣọ àti bàtà lẹ́yìn ìnáwó tí a ṣe lánàá
1
yo
Àlàkẹ́ ṣiṣẹ́ mìíràn lẹ́yìn iṣẹ́ ìjọba
Àlàkẹ́ ṣiṣẹ́ tó pọ̀ lánàá
Lẹ́yìn iṣẹ́ ìjọba ti Àlàkẹ́ ń ṣe, ó tún wá nǹkan mìíràn fi pawọ́dà
0
yo
Àlàkẹ́ ṣiṣẹ́ mìíràn lẹ́yìn iṣẹ́ ìjọba
Àlàkẹ́ ṣiṣẹ́ tó pọ̀ lánàá
Lẹ́yìn tí ìjọba mú Àlàkẹ́, kò ri iṣẹ́ gbà mọ
1
yo
Bí Okùnọlá ò bá ṣiṣẹ́, kò lè rí oúnjẹ jẹ
Bí Okùnọlá ò bá ṣiṣẹ́, kò lè sùn
Bí ọwọ́ Okùnọlá ò bá ṣe, ẹnu rẹ̀ kòlè jẹ
1
yo
Bí Okùnọlá ò bá ṣiṣẹ́, kò lè rí oúnjẹ jẹ
Bí Okùnọlá ò bá ṣiṣẹ́, kò lè sùn
Okùnọlá ń fi iṣẹ́ ọwọ́ rẹ̀ ra oúnjẹ sí ẹnu ara rẹ̀
0
yo