diacritcs
stringlengths 1
36.7k
| no_diacritcs
stringlengths 1
35.5k
|
---|---|
A kò ní ṣí olódodo ní ipò pada lae,títí ayé ni a óo sì máa ranti rẹ̀.Ẹ sẹ́ ẹni Ọlọrun ati olódodo, ẹ wá bèèrè pé kí wọ́n dá apànìyàn sílẹ̀ fun yín; Sa gbogbo ipá rẹ láti tètè wá sọ́dọ̀ mi. wọ́n ní, “A kò ní fetí sì ọ̀rọ̀ tí ò ń bá wa sọ lórúkọ OLUWA. Joṣua bá yipada, ó gba ìlú Hasori, ó sì fi idà pa ọba wọn, nítorí pé Hasori ni olú-ìlú ìjọba ilẹ̀ náà tẹ́lẹ̀ rí. ati òróró ìyàsímímọ́, ati turari olóòórùn dídùn fún ibi mímọ́. Gbogbo ohun tí mo pa láṣẹ fún ọ patapata ni wọn yóo ṣe bí mo ti pa á láṣẹ.”Èyíkéyìí ninu àwọn ọmọ Aaroni tí ó bá fi ẹ̀jẹ̀ ati ọ̀rá ẹran náà rúbọ ni ó ni itan ọ̀tún ẹran náà gẹ́gẹ́ bí ìpín tirẹ̀. Kò sí ẹni tíí yan ara rẹ̀ sí ipò yìí. Ṣugbọn àwọn tí Ọlọrun bá pè ni à ń yàn, bíi Aaroni. Nígbà tí ọkunrin náà rí i pé òun kò lè dá Jakọbu, ó fi ọwọ́ kan kòtò itan rẹ̀, eegun itan Jakọbu bá yẹ̀ níbi tí ó ti ń bá a jìjàkadì. Angẹli náà bá mú àwo turari yìí, ó bu iná láti orí pẹpẹ ìrúbọ kún inú rẹ̀, ó bá jù ú sí orí ilẹ̀ ayé. Ààrá bá bẹ̀rẹ̀ sí sán, mànàmáná ń kọ, ilẹ̀ bẹ̀rẹ̀ sí mì tìtì. Gbójú sókè, kí o wò yíká,gbogbo àwọn ọmọ rẹ péjọ, wọ́n tọ̀ ọ́ wá.OLUWA fi ara rẹ̀ búra pé,o óo gbé wọn wọ̀ bí nǹkan ọ̀ṣọ́ ara.O óo wọ̀ wọ́n bí ìgbà tí iyawo kó ohun ọ̀ṣọ́ wọ̀.Ẹ̀mí mi yóo ní ànító ati àníṣẹ́kù;n óo sì fi ayọ̀ kọ orin ìyìn sí ọ.O bá àwọn onigbeeraga wí, àwọn ẹni ègún,tí wọn kò pa òfin rẹ mọ́.It is on the day of relaxation that the lazy person experiences regret. | A ko ni si olododo ni ipo pada lae,titi aye ni a oo si maa ranti re.E se eni Olorun ati olododo, e wa beere pe ki won da apaniyan sile fun yin; Sa gbogbo ipa re lati tete wa sodo mi. won ni, “A ko ni feti si oro ti o n ba wa so loruko OLUWA. Josua ba yipada, o gba ilu Hasori, o si fi ida pa oba won, nitori pe Hasori ni olu-ilu ijoba ile naa tele ri. ati ororo iyasimimo, ati turari olooorun didun fun ibi mimo. Gbogbo ohun ti mo pa lase fun o patapata ni won yoo se bi mo ti pa a lase.”Eyikeyii ninu awon omo Aaroni ti o ba fi eje ati ora eran naa rubo ni o ni itan otun eran naa gege bi ipin tire. Ko si eni tii yan ara re si ipo yii. Sugbon awon ti Olorun ba pe ni a n yan, bii Aaroni. Nigba ti okunrin naa ri i pe oun ko le da Jakobu, o fi owo kan koto itan re, eegun itan Jakobu ba ye nibi ti o ti n ba a jijakadi. Angeli naa ba mu awo turari yii, o bu ina lati ori pepe irubo kun inu re, o ba ju u si ori ile aye. Aara ba bere si san, manamana n ko, ile bere si mi titi. Gboju soke, ki o wo yika,gbogbo awon omo re pejo, won to o wa.OLUWA fi ara re bura pe,o oo gbe won wo bi nnkan oso ara.O oo wo won bi igba ti iyawo ko ohun oso wo.Emi mi yoo ni anito ati aniseku;n oo si fi ayo ko orin iyin si o.O ba awon onigbeeraga wi, awon eni egun,ti won ko pa ofin re mo.It is on the day of relaxation that the lazy person experiences regret. |
Ó sàn láti máa gbé kọ̀rọ̀ kan lókè àjà, ju pé kí eniyan máa bá oníjàngbọ̀n obinrin gbé ilé lọ.àwọn Juu péjọ ninu àwọn ìlú wọn ní àwọn ìgbèríko ilẹ̀ Ahasu-erusi ọba, wọ́n múra láti bá àwọn tí wọ́n fẹ́ pa wọ́n run jà. Kò sí ẹni tí ó lè kò wọ́n lójú nítorí pé gbogbo àwọn eniyan ni wọ́n ń bẹ̀rù wọn. A óo yọ ẹnikẹ́ni tí ó bá jẹ ẹ̀jẹ̀ kúrò lára àwọn eniyan Ọlọrun.” Mú ojú ìbáwí kúrò lára mi,kí inú mi lè dùn kí n tó kọjá lọ;àní, kí n tó ṣe aláìsí.”Oòrùn yọ kí ó tó kọjá Penueli, nítorí pé títiro ni ó ń tiro lọ nítorí itan rẹ̀. The white man sells merchandise with the name brand still attached; the Ègùn person sells cloth still in its bundle. | O san lati maa gbe koro kan loke aja, ju pe ki eniyan maa ba onijangbon obinrin gbe ile lo.awon Juu pejo ninu awon ilu won ni awon igberiko ile Ahasu-erusi oba, won mura lati ba awon ti won fe pa won run ja. Ko si eni ti o le ko won loju nitori pe gbogbo awon eniyan ni won n beru won. A oo yo enikeni ti o ba je eje kuro lara awon eniyan Olorun.” Mu oju ibawi kuro lara mi,ki inu mi le dun ki n to koja lo;ani, ki n to se alaisi.”Oorun yo ki o to koja Penueli, nitori pe titiro ni o n tiro lo nitori itan re. The white man sells merchandise with the name brand still attached; the Egun person sells cloth still in its bundle. |
Tọ́ mi sí ọ̀nà nípa òfin rẹ,nítorí pé mo láyọ̀ ninu rẹ̀.Next year's pounded yam will still find some stew. | To mi si ona nipa ofin re,nitori pe mo layo ninu re.Next year's pounded yam will still find some stew. |
Wọ́n gbé e lọ sí ilé Dagoni, oriṣa wọn; wọ́n sì gbé e kalẹ̀ lẹ́gbẹ̀ẹ́ ère oriṣa náà. àwọn ará Babiloni ati gbogbo àwọn ará Kalidea láti Pekodi, ati Ṣoa ati Koa, pẹlu gbogbo àwọn ará Asiria: àwọn ọdọmọkunrin tí ojú wọn fanimọ́ra, àwọn gomina, ati àwọn ọ̀gágun, tí gbogbo wọn jẹ́ olórí ogun, tí wọ́n sì ń gun ẹṣin. Ẹẹmẹta ni mo bẹ Oluwa nítorí rẹ̀ pé kí ó mú un kúrò lára mi. OLUWA bá sọ fún Mose pé, “Yan aadọrin ninu àwọn àgbààgbà Israẹli, àwọn tí àwọn ọmọ Israẹli mọ̀ ní olórí, kí o sì mú wọn wá sí ẹnu ọ̀nà Àgọ́ Àjọ. Kí wọ́n dúró pẹlu rẹ níbẹ̀. Kékeré ejò, má foore ṣe é. | Won gbe e lo si ile Dagoni, orisa won; won si gbe e kale legbee ere orisa naa. awon ara Babiloni ati gbogbo awon ara Kalidea lati Pekodi, ati Soa ati Koa, pelu gbogbo awon ara Asiria: awon odomokunrin ti oju won fanimora, awon gomina, ati awon ogagun, ti gbogbo won je olori ogun, ti won si n gun esin. Eemeta ni mo be Oluwa nitori re pe ki o mu un kuro lara mi. OLUWA ba so fun Mose pe, “Yan aadorin ninu awon agbaagba Israeli, awon ti awon omo Israeli mo ni olori, ki o si mu won wa si enu ona Ago Ajo. Ki won duro pelu re nibe. Kekere ejo, ma foore se e. |
Ìjọba tí Ọlọrun fún ọ wà lae ati laelae.Ọ̀pá àṣẹ rẹ, ọ̀pá àṣẹ ẹ̀tọ́ ni.Ọlọrun tún ní, “Ti ọwọ́ rẹ bọ abíyá pada.” Mose sì ti ọwọ́ bọ abíyá rẹ̀ pada; nígbà tí ó yọ ọ́ jáde, ọwọ́ rẹ̀ pada sí bí ó ti wà tẹ́lẹ̀. Lẹ́yìn náà ó mọ odi ìta sí ìlú Dafidi, ní apá ìwọ̀ oòrùn Gihoni, ní àfonífojì, ati sí ẹnubodè ẹja; ó mọ ọ́n tí ó ga yípo Ofeli. Ó kó àwọn ọ̀gágun sinu àwọn ìlú olódi ní Juda. Àwọn tí wọ́n bá ṣẹ́kù láti àwọn orílẹ̀-èdè gbogbo tí ó gbógun ti ilẹ̀ Jerusalẹmu yóo máa wá lọdọọdun láti sin Ọba, OLUWA àwọn ọmọ ogun, ní ìlú Jerusalẹmu ati láti ṣe Àjọ̀dún Àgọ́. Gbogbo ẹja tí ó wà ninu odò náà kú, odò sì bẹ̀rẹ̀ sí rùn tóbẹ́ẹ̀ tí àwọn ará Ijipti kò fi lè mu omi rẹ̀. Ẹ̀jẹ̀ sì wà níbi gbogbo jákèjádò ilẹ̀ Ijipti. Òrìṣà tó ní tÒgún kì í ṣe ọ̀nà ò ní rí nńkan jẹ lásìkò tó fẹ́. | Ijoba ti Olorun fun o wa lae ati laelae.Opa ase re, opa ase eto ni.Olorun tun ni, “Ti owo re bo abiya pada.” Mose si ti owo bo abiya re pada; nigba ti o yo o jade, owo re pada si bi o ti wa tele. Leyin naa o mo odi ita si ilu Dafidi, ni apa iwo oorun Gihoni, ni afonifoji, ati si enubode eja; o mo on ti o ga yipo Ofeli. O ko awon ogagun sinu awon ilu olodi ni Juda. Awon ti won ba seku lati awon orile-ede gbogbo ti o gbogun ti ile Jerusalemu yoo maa wa lodoodun lati sin Oba, OLUWA awon omo ogun, ni ilu Jerusalemu ati lati se Ajodun Ago. Gbogbo eja ti o wa ninu odo naa ku, odo si bere si run tobee ti awon ara Ijipti ko fi le mu omi re. Eje si wa nibi gbogbo jakejado ile Ijipti. Orisa to ni tOgun ki i se ona o ni ri nnkan je lasiko to fe. |
Lẹ́yìn náà, Ẹ̀mí gbé Jesu lọ sí aṣálẹ̀ kí Èṣù lè dán an wò. Since you claim to be a seasoned rider, how come your horse has gone lame? | Leyin naa, Emi gbe Jesu lo si asale ki Esu le dan an wo. Since you claim to be a seasoned rider, how come your horse has gone lame? |
Ojú rẹ̀ dàbí ọ̀wọ́ iná. Ó dé adé pupọ tí a kọ orúkọ sí, orúkọ tí ẹnikẹ́ni kò mọ̀ àfi òun alára. Ẹ kò ní jẹ̀bi nígbà tí ẹ bá jẹ ẹ́, níwọ̀n ìgbà tí ẹ ti san ìdámẹ́wàá ninu èyí tí ó dára jù. Ẹ ṣọ́ra kí ẹ má baà sọ ọrẹ mímọ́ àwọn ọmọ Israẹli di àìmọ́ nípa jíjẹ wọ́n láìsan ìdámẹ́wàá wọn. Bí bẹ́ẹ̀ kọ́, ẹ óo kú.”Ọrẹ tirẹ̀ ni: àwo fadaka kan, tí ìwọ̀n rẹ̀ jẹ́ aadoje (130) ṣekeli, pẹlu abọ́ fadaka kan tí ìwọ̀n rẹ̀ jẹ́ aadọrin ṣekeli. Ìwọ̀n tí wọn ń lò ní ibi mímọ́ ni wọ́n fi wọ̀n ọ́n. Àwo ati abọ́ náà kún fún ẹbọ ohun jíjẹ. Odò Jọdani ni ààlà rẹ̀ ní apá ìlà oòrùn. Èyí ni ilẹ̀ tí a pín fún ẹ̀yà Bẹnjamini ní ìdílé-ìdílé, pẹlu àwọn ààlà ilẹ̀ ìdílé kọ̀ọ̀kan.One-who-is-tight-with-the-right-and-tight-with-left-without-alienating-either; what one will find in that characterization is a lie. | Oju re dabi owo ina. O de ade pupo ti a ko oruko si, oruko ti enikeni ko mo afi oun alara. E ko ni jebi nigba ti e ba je e, niwon igba ti e ti san idamewaa ninu eyi ti o dara ju. E sora ki e ma baa so ore mimo awon omo Israeli di aimo nipa jije won laisan idamewaa won. Bi bee ko, e oo ku.”Ore tire ni: awo fadaka kan, ti iwon re je aadoje (130) sekeli, pelu abo fadaka kan ti iwon re je aadorin sekeli. Iwon ti won n lo ni ibi mimo ni won fi won on. Awo ati abo naa kun fun ebo ohun jije. Odo Jodani ni aala re ni apa ila oorun. Eyi ni ile ti a pin fun eya Benjamini ni idile-idile, pelu awon aala ile idile kookan.One-who-is-tight-with-the-right-and-tight-with-left-without-alienating-either; what one will find in that characterization is a lie. |
Ẹ ṣọ́ra gidigidi, ẹ má gbàgbé majẹmu tí OLUWA Ọlọrun yín ba yín dá, ẹ má sì yá èrekére fún ara yín, ní àwòrán ohunkohun, nítorí pé, OLUWA Ọlọrun yín lòdì sí i. Ìṣirò ohun tí wọ́n lò fún kíkọ́ àgọ́ ẹ̀rí wíwà OLUWA nìyí: Mose ni ó pàṣẹ pé kí ọmọ Lefi ṣe ìṣirò àwọn ohun tí wọ́n lò lábẹ́ àkóso Itamari ọmọ Aaroni, alufaa.Ninu ilẹ̀ náà ni àwọn ìlú tí wọ́n wà lórí òkè wà, ati àwọn tí wọ́n wà ní ẹsẹ̀ òkè, ati àwọn tí wọ́n wà ní Araba, ní gẹ̀rẹ́gẹ̀rẹ́ òkè, ní aṣálẹ̀, ati ní Nẹgẹbu. Àwọn tí wọ́n ni ilẹ̀ yìí tẹ́lẹ̀ rí ni àwọn ará Hiti ati àwọn ará Amori, àwọn ará Kenaani ati àwọn ará Perisi, àwọn ará Hifi, ati àwọn ará Jebusi. Di àpẹẹrẹ ẹ̀kọ́ tí ó yẹ, tí o ti gbà láti ọ̀dọ̀ mi mú, pẹlu igbagbọ ati ìfẹ́ tí ó wà ninu Kristi Jesu. Ṣé o kò tíì mọ̀,o kò sì tíì gbọ́pé Ọlọrun ayérayé ni OLUWA,Ẹlẹ́dàá gbogbo ayé.Kì í rẹ̀ ẹ́, bẹ́ẹ̀ ni agara kì í dá a.Àwámárìídìí ni òye rẹ̀.Bí o ní ọ̀pọ̀ oògùn, tí o ní èké, kò níí jẹ́; orí ẹní jẹ́ ó ju ewé lọ; ìpín jà ó ju oògùn lọ. | E sora gidigidi, e ma gbagbe majemu ti OLUWA Olorun yin ba yin da, e ma si ya erekere fun ara yin, ni aworan ohunkohun, nitori pe, OLUWA Olorun yin lodi si i. Isiro ohun ti won lo fun kiko ago eri wiwa OLUWA niyi: Mose ni o pase pe ki omo Lefi se isiro awon ohun ti won lo labe akoso Itamari omo Aaroni, alufaa.Ninu ile naa ni awon ilu ti won wa lori oke wa, ati awon ti won wa ni ese oke, ati awon ti won wa ni Araba, ni geregere oke, ni asale, ati ni Negebu. Awon ti won ni ile yii tele ri ni awon ara Hiti ati awon ara Amori, awon ara Kenaani ati awon ara Perisi, awon ara Hifi, ati awon ara Jebusi. Di apeere eko ti o ye, ti o ti gba lati odo mi mu, pelu igbagbo ati ife ti o wa ninu Kristi Jesu. Se o ko tii mo,o ko si tii gbope Olorun ayeraye ni OLUWA,Eledaa gbogbo aye.Ki i re e, bee ni agara ki i da a.Awamariidii ni oye re.Bi o ni opo oogun, ti o ni eke, ko nii je; ori eni je o ju ewe lo; ipin ja o ju oogun lo. |