diacritcs
stringlengths
1
36.7k
no_diacritcs
stringlengths
1
35.5k
ni ìpinnu (Ọlọrun) n bẹ fún.
ni ipinnu (Olorun) n be fun.
40. Allah A máa pa ohun tí ô bá
40. Allah A maa pa ohun ti o ba
wù Ú rẹ̀. Ò sì máa n fi ìdí ohun
wu U re. O si maa n fi idi ohun
ti ô bá wù Ú múlẹ̀. Ọdò Rẹ̀ sì ni
ti o ba wu U mule. Odo Re si ni
orísun àwọn Àṣẹ wà.
orisun awon Ase wa.
41. Bi A bá fi apá kan ohun tí A
41. Bi A ba fi apa kan ohun ti A
fi n dẹrù bà wọn hàn ọ, tàbí A fi
fi n deru ba won han o, tabi A fi
ikú pa ọ, (ohun kékeré) ni, ohun
iku pa o, (ohun kekere) ni, ohun
ti ô jẹ iwọ tìrẹ ni JÍJẸ iṣẹ náà
ti o je iwo tire ni JIJE ise naa
dòpin, ti wa sì ni ÌṢIrÒ.
dopin, ti wa si ni ISIrO.
42. Wọn kò ha rí i ni pé Àwa ni
42. Won ko ha ri i ni pe Awa ni
À ni bẹ ilẹ̀ wò tí A sì fi dín in kù
A ni be ile wo ti A si fi din in ku
ni ẹ̀bẹ̀ẹ̀bá rẹ̀. Allah ni ô n dá ẹjJỌ,
ni ebeeba re. Allah ni o n da ejJO,
tí ẹnìkan kò lẹ̀ yí ìdájọ Rẹ̀ padà.
ti enikan ko le yi idajo Re pada.
Ô sì yara ní ìṣirò ṣíṣe.
O si yara ni isiro sise.
43. Dájúdájú àwọn tô. ṣíwájú
43. Dajudaju awon to. siwaju
wọn ti pa ẹ̀te rí, ṣùgbọn ti Allah niNígbà tí Saulu ati àwọn ọmọ ogun rẹ̀ gbọ́, ẹ̀rù bà wọ́n gidigidi.Bí ó ti wọ ilé Ọlọrun lọ, tí ó mú burẹdi tí ó wà lórí tabili níwájú Oluwa, tí ó jẹ ẹ́, tí ó tún fún àwọn tí ó wà pẹlu rẹ̀, bẹ́ẹ̀ sì ni ẹnikẹ́ni kò gbọdọ̀ jẹ ẹ́ àfi àwọn alufaa nìkan?” Kí òkun ati ohun gbogbo tó wà ninu rẹ̀ hó yèè,kí pápá oko búsáyọ̀, ati gbogbo ẹ̀dá tó wà ninu rẹ̀.Statements must be clarified; if they are not, they become muddy...
won ti pa ete ri, sugbon ti Allah niNigba ti Saulu ati awon omo ogun re gbo, eru ba won gidigidi.Bi o ti wo ile Olorun lo, ti o mu buredi ti o wa lori tabili niwaju Oluwa, ti o je e, ti o tun fun awon ti o wa pelu re, bee si ni enikeni ko gbodo je e afi awon alufaa nikan?” Ki okun ati ohun gbogbo to wa ninu re ho yee,ki papa oko busayo, ati gbogbo eda to wa ninu re.Statements must be clarified; if they are not, they become muddy...
One must always be clear in one's speeches or intentions. The second part about a woman's genitals is gratuitous flippancy; it takes advantage of the syllable là (in Ẹ̀là), which means “clarify,” and also denotes the action of passing one's loincloth between one's split thighs so as to cover one's genitalia.
One must always be clear in one's speeches or intentions. The second part about a woman's genitals is gratuitous flippancy; it takes advantage of the syllable la (in Ela), which means “clarify,” and also denotes the action of passing one's loincloth between one's split thighs so as to cover one's genitalia.
Dípò kí ẹ ṣe bẹ́ẹ̀, onigbagbọ ń pe onigbagbọ lẹ́jọ́ níwájú àwọn alaigbagbọ!Òdodo ni gbogbo ọ̀rọ̀ ẹnu mi, kò sí ìtànjẹ tabi ọ̀rọ̀ àrékérekè ninu wọn.Kì í wá ṣe fún orílẹ̀-èdè wọn nìkan, ṣugbọn kí àwọn ọmọ Ọlọrun tí ó fọ́nká lè papọ̀ di ọ̀kan.Nítorí gbogbo ìlérí Ọlọrun di “bẹ́ẹ̀ ni” ninu rẹ̀. Ìdí tí a fi ń ṣe “Amin” ní orúkọ rẹ̀ nìyí, nígbà tí a bá ń fi ògo fún Ọlọrun. Ṣugbọn àkókò ń bọ̀, ó tilẹ̀ dé tán báyìí, nígbà tí àwọn tí ń jọ́sìn tòótọ́ yóo máa sin Baba ní ẹ̀mí ati ní òtítọ́, nítorí irú àwọn bẹ́ẹ̀ ni Baba ń wá kí wọ́n máa sin òun. Wọ́n péjọ ní Jerusalẹmu ní oṣù kẹta ọdún kẹẹdogun ìjọba Asa. Mo wí ninu ọkàn mi pé, n óo dán ìgbádùn wò; n óo gbádùn ara mi, ṣugbọn, èyí pàápàá, asán ni. “Èmi Atasasesi ọba pàṣẹ fún àwọn olùtọ́jú ilé ìṣúra ní agbègbè òdìkejì odò láti pèsè gbogbo nǹkan tí Ẹsira, alufaa akọ̀wé òfin Ọlọrun ọ̀run, bá fẹ́ fún un. Àwọn Kerubu náà na ìyẹ́ wọn bo ìtẹ́ àánú náà; wọ́n kọjú sí ara wọn, wọ́n ń wo ìtẹ́ àánú.Joabu bá tọ Dafidi ọba lọ, ó sì sọ ohun tí Absalomu wí fún un. Ọba ranṣẹ pe Absalomu, ó sì wá sọ́dọ̀ ọba. Ó wólẹ̀, ó dojúbolẹ̀ níwájú rẹ̀, ọba bá fi ẹnu kò ó ní ẹnu.Kí ẹ̀kọ́ mi kí ó máa rọ̀ bí òjò,àní, bí ọ̀wààrà òjò tíí dẹ ewébẹ̀ lọ́rùn;kí ó sì máa sẹ̀ bí ìrì,bí òjò wẹ́rẹ́wẹ́rẹ́ tíí tu koríko lára.(Àwọn ni ọmọ tí Lea bí fún Jakọbu ní Padani-aramu ati Dina, ọmọ rẹ̀ obinrin.) Gbogbo àwọn ọmọ rẹ̀ lọkunrin ati lobinrin jẹ́ mẹtalelọgbọn.Nítorí náà, n kò ní fi ìyà jẹ Jerusalẹmu nígbà tí ó wà láàyè, n óo jẹ́ kí ó kú ní alaafia.” ’ ”Àwọn ọkunrin náà sì lọ jíṣẹ́ fún Josaya ọba.ibi tí OLUWA Ọlọrun yín bá yàn láti fi ibùgbé rẹ̀ sí nígbà náà, ni kí ẹ kó gbogbo àwọn nǹkan tí mo pa láṣẹ fun yín wa, ẹbọ sísun yín ati àwọn ẹbọ mìíràn, ìdámẹ́wàá yín, ati ọrẹ, ati gbogbo ẹ̀jẹ́ yín tí ẹ bá jẹ́ fún OLUWA. Aláìsàn náà dáhùn pé, “Alàgbà, n kò ní ẹni tí yóo gbé mi sinu adágún nígbà tí omi bá rú pọ̀, nígbà tí n óo bá fi dé ibẹ̀, ẹlòmíràn á ti wọ inú omi ṣiwaju mi.”Ọlọgbọ́n ńdẹ ihò, ọ̀mọ̀rànán dúró tì í; ọlọgbọ́n ní “Háà, ó jáde!”Ọ̀mọ̀rán ní “Háà, mo kì í!”Ọlọgbọ́n ní “Kí lo kì?” Ọ̀mọ̀rán ní “Kí nìwọ náà-á ló jáde?”
Dipo ki e se bee, onigbagbo n pe onigbagbo lejo niwaju awon alaigbagbo!Ododo ni gbogbo oro enu mi, ko si itanje tabi oro arekereke ninu won.Ki i wa se fun orile-ede won nikan, sugbon ki awon omo Olorun ti o fonka le papo di okan.Nitori gbogbo ileri Olorun di “bee ni” ninu re. Idi ti a fi n se “Amin” ni oruko re niyi, nigba ti a ba n fi ogo fun Olorun. Sugbon akoko n bo, o tile de tan bayii, nigba ti awon ti n josin tooto yoo maa sin Baba ni emi ati ni otito, nitori iru awon bee ni Baba n wa ki won maa sin oun. Won pejo ni Jerusalemu ni osu keta odun keedogun ijoba Asa. Mo wi ninu okan mi pe, n oo dan igbadun wo; n oo gbadun ara mi, sugbon, eyi paapaa, asan ni. “Emi Atasasesi oba pase fun awon olutoju ile isura ni agbegbe odikeji odo lati pese gbogbo nnkan ti Esira, alufaa akowe ofin Olorun orun, ba fe fun un. Awon Kerubu naa na iye won bo ite aanu naa; won koju si ara won, won n wo ite aanu.Joabu ba to Dafidi oba lo, o si so ohun ti Absalomu wi fun un. Oba ranse pe Absalomu, o si wa sodo oba. O wole, o dojubole niwaju re, oba ba fi enu ko o ni enu.Ki eko mi ki o maa ro bi ojo,ani, bi owaara ojo tii de ewebe lorun;ki o si maa se bi iri,bi ojo werewere tii tu koriko lara.(Awon ni omo ti Lea bi fun Jakobu ni Padani-aramu ati Dina, omo re obinrin.) Gbogbo awon omo re lokunrin ati lobinrin je metalelogbon.Nitori naa, n ko ni fi iya je Jerusalemu nigba ti o wa laaye, n oo je ki o ku ni alaafia.” ’ ”Awon okunrin naa si lo jise fun Josaya oba.ibi ti OLUWA Olorun yin ba yan lati fi ibugbe re si nigba naa, ni ki e ko gbogbo awon nnkan ti mo pa lase fun yin wa, ebo sisun yin ati awon ebo miiran, idamewaa yin, ati ore, ati gbogbo eje yin ti e ba je fun OLUWA. Alaisan naa dahun pe, “Alagba, n ko ni eni ti yoo gbe mi sinu adagun nigba ti omi ba ru po, nigba ti n oo ba fi de ibe, elomiran a ti wo inu omi siwaju mi.”Ologbon nde iho, omoranan duro ti i; ologbon ni “Haa, o jade!”Omoran ni “Haa, mo ki i!”Ologbon ni “Ki lo ki?” Omoran ni “Ki niwo naa-a lo jade?”
Nítorí náà, n óo sọ iná sí orí odi ìlú Raba, yóo sì jó ibi ààbò rẹ̀ ní àjórun. Ariwo yóo sọ ní ọjọ́ ogun, omi òkun yóo ru sókè ní ọjọ́ ìjì; “Sọ fún Eleasari ọmọ Aaroni, alufaa pé kí ó kó àwọn àwo turari wọ̀n-ọn-nì kúrò láàrin àjókù àwọn eniyan náà. Kí ó sì da iná inú wọn káàkiri jìnnà jìnnà nítorí àwọn àwo turari náà jẹ́ mímọ́. It is fitting for everybody to bargain to reduce the cost of dyeing clothes, but not the bed wetter.
Nitori naa, n oo so ina si ori odi ilu Raba, yoo si jo ibi aabo re ni ajorun. Ariwo yoo so ni ojo ogun, omi okun yoo ru soke ni ojo iji; “So fun Eleasari omo Aaroni, alufaa pe ki o ko awon awo turari won-on-ni kuro laarin ajoku awon eniyan naa. Ki o si da ina inu won kaakiri jinna jinna nitori awon awo turari naa je mimo. It is fitting for everybody to bargain to reduce the cost of dyeing clothes, but not the bed wetter.
Ọgbọ́n tí ọ̀pọ̀lọ́ fi pa ẹfọ̀n ló fi ńjẹ ẹ́.
Ogbon ti opolo fi pa efon lo fi nje e.
Lẹ́yìn tí wọ́n tún halẹ̀ mọ́ wọn, wọ́n dá wọn sílẹ̀, nítorí wọn kò rí ọ̀nà tí wọn ìbá fi jẹ wọ́n níyà, nítorí àwọn eniyan. Gbogbo eniyan ni wọ́n sì ń fi ìyìn fún Ọlọrun fún ohun tí ó ti ṣẹlẹ̀. Nítorí Ọlọrun fi sí ọkàn wọn láti ní ète kan náà, pé àwọn yóo fi ìjọba àwọn fún ẹranko náà títí gbogbo ohun tí Ọlọrun ti sọ yóo fi ṣẹ.Yìnyín ń bọ́, mànàmáná sì ń kọ yànràn ninu yìnyín náà. Yìnyín náà pọ̀ tóbẹ́ẹ̀ gẹ́ẹ́; kò tíì sí irú rẹ̀ rí ní gbogbo ilẹ̀ Ijipti láti ìgbà tí ó ti di orílẹ̀-èdè. Alufaa yóo mú òróró tí ó kù ní ọwọ́ rẹ̀ yóo sì fi ra orí ẹni tí wọ́n fẹ́ wẹ̀ mọ́, láti fi ṣe ètùtù fún un níwájú OLUWA. Láìjẹ́ pé wọ́n rí ohunkohun tí ó fi jẹ̀bi ikú, wọ́n ní kí Pilatu pa á. An idiot child that plays with ìdò flowers.
Leyin ti won tun hale mo won, won da won sile, nitori won ko ri ona ti won iba fi je won niya, nitori awon eniyan. Gbogbo eniyan ni won si n fi iyin fun Olorun fun ohun ti o ti sele. Nitori Olorun fi si okan won lati ni ete kan naa, pe awon yoo fi ijoba awon fun eranko naa titi gbogbo ohun ti Olorun ti so yoo fi se.Yinyin n bo, manamana si n ko yanran ninu yinyin naa. Yinyin naa po tobee gee; ko tii si iru re ri ni gbogbo ile Ijipti lati igba ti o ti di orile-ede. Alufaa yoo mu ororo ti o ku ni owo re yoo si fi ra ori eni ti won fe we mo, lati fi se etutu fun un niwaju OLUWA. Laije pe won ri ohunkohun ti o fi jebi iku, won ni ki Pilatu pa a. An idiot child that plays with ido flowers.
Ojú iná kọ́ lewùrà ńhurun.
Oju ina ko lewura nhurun.
Wọ́n sọ fún Abimeleki pé gbogbo àwọn tí wọ́n wà ní ilé ìṣọ́ tí ó wà ní Ṣekemu ti kó ara wọn jọ sí ibìkan. N óo pa gbogbo àwọn ará Aṣidodu run ati ọba Aṣikeloni; n óo jẹ ìlú Ekironi níyà, àwọn ará Filistia yòókù yóo sì ṣègbé.” OLUWA Ọlọrun ló sọ bẹ́ẹ̀. Bí ẹnìkan bá ń kọ́ àwọn eniyan ní ẹ̀kọ́ mìíràn, tí kò mọ ẹ̀kọ́ tí ó yè, ẹ̀kọ́ ti Oluwa wa Jesu Kristi, ati ẹ̀kọ́ ẹ̀sìn tí ó pé, Nígbà tí àwọn ọ̀tá mi pẹ̀yìndà,wọ́n ṣubú, wọ́n sì parun níwájú rẹ.Akọ mààlúù kékeré kan, àgbò kan, ọ̀dọ́ àgbò kan ọlọ́dún kan, fún ẹbọ sísun, Ó kọ àgọ́ àwọn ọmọ Josẹfu sílẹ̀;kò sì yan ẹ̀yà Efuraimu;Ọlọrun wí fún un pé, “Jakọbu ni orúkọ rẹ, ṣugbọn wọn kò ní pè ọ́ ní Jakọbu mọ́, Israẹli ni orúkọ rẹ yóo máa jẹ́.” Bẹ́ẹ̀ ni Ọlọrun ṣe sọ ọ́ ní Israẹli. 30. 'Nígbà tí Mo ti dá a (ní
Won so fun Abimeleki pe gbogbo awon ti won wa ni ile iso ti o wa ni Sekemu ti ko ara won jo si ibikan. N oo pa gbogbo awon ara Asidodu run ati oba Asikeloni; n oo je ilu Ekironi niya, awon ara Filistia yooku yoo si segbe.” OLUWA Olorun lo so bee. Bi enikan ba n ko awon eniyan ni eko miiran, ti ko mo eko ti o ye, eko ti Oluwa wa Jesu Kristi, ati eko esin ti o pe, Nigba ti awon ota mi peyinda,won subu, won si parun niwaju re.Ako maaluu kekere kan, agbo kan, odo agbo kan olodun kan, fun ebo sisun, O ko ago awon omo Josefu sile;ko si yan eya Efuraimu;Olorun wi fun un pe, “Jakobu ni oruko re, sugbon won ko ni pe o ni Jakobu mo, Israeli ni oruko re yoo maa je.” Bee ni Olorun se so o ni Israeli. 30. 'Nigba ti Mo ti da a (ni
àdápé) tán, tí Mo sì mí Eémí Mi
adape) tan, ti Mo si mi Eemi Mi
sínú rẹ̀ (Mo wí p€) 'Ẹ wúòlẹ̀ kí ẹ sì
sinu re (Mo wi p€) 'E wuole ki e si
tẹríba fún un.
teriba fun un.
31. Nitorí náà, gbogbo. àwọn
31. Nitori naa, gbogbo. awon
màláíkà pátápátá sì wúlẹ̀.
malaika patapata si wule.
32. Àyàfi Iblis; ô kò láti j$ òkan
32. Ayafi Iblis; o ko lati j$ okan
nínú àwọn t6 tẹríba.
ninu awon t6 teriba.
33. (Ọlọrun) sì wí pé, "Ìwọ Iblis,
33. (Olorun) si wi pe, "Iwo Iblis,
Ki lé ṣe ọ tí o kò fi ní jẹ ọkan
Ki le se o ti o ko fi ni je okan
nínú àwọn téô tẹríba?
ninu awon teo teriba?
34. Ô dáhùn pé, 'Emi kò ní tẹríba
34. O dahun pe, 'Emi ko ni teriba
fún ẹni tí O dá pẹ̀lú amọ sísun tí
fun eni ti O da pelu amo sisun ti
A mú jáde láti inú amọ tútù.'
A mu jade lati inu amo tutu.'
35. (Ọlọrun) wí pé, 'TO ba ri bẹ̀ẹ̀,
35. (Olorun) wi pe, 'TO ba ri bee,
Jáde nísinsìnyìí, nitorí pé o ti di
Jade nisinsinyii, nitori pe o ti di
ẹni ẹ̀kọ.
eni eko.
36. Dájúdájú ẹ̀gún (MI) yòò máa
36. Dajudaju egun (MI) yoo maa
bẹ lòrí rẹ̀ títí di Ọjọ Idájọ.'
be lori re titi di Ojo Idajo.'
37. Ô wí pé, 'Olúwa mi, tò bá rí
37. O wi pe, 'Oluwa mi, to ba ri
bẹ̀ẹ̀, lọ mi lára títí di ọjọ tí a ô
bee, lo mi lara titi di ojo ti a o
gbé wọn dìde.
gbe won dide.
38. (Ọlọrun) wí pé, 'O ti wà nínú
38. (Olorun) wi pe, 'O ti wa ninu
àwọn tí a lọ lara,
awon ti a lo lara,
39. "Titi di ọjọ tí a yàn.
39. "Titi di ojo ti a yan.
40. Ô dáhùn pé, 'Olúwa mi,
40. O dahun pe, 'Oluwa mi,
níwọn ìgbà tí O ti ṣe mí lẹni òfò,
niwon igba ti O ti se mi leni ofo,
dájúdájú Emi yòò ṣe (àwọn
dajudaju Emi yoo se (awon
nìkan búburú) lọṣòọ fún wọn lori
nikan buburu) losoo fun won lori
ilẹ̀, òmi yòò sì tún ṣi gbogbo wọn
ile, omi yoo si tun si gbogbo won
lọnà.
lona.
Eegun tí a bá so mọ́ ajá lọ́rùn, kì í ṣán an.
Eegun ti a ba so mo aja lorun, ki i san an.
Ọba nìkan ni ó lè jókòó níbẹ̀ láti jẹun níwájú OLUWA. Yóo gba ẹnu ọ̀nà ìloro wọlé, ibẹ̀ náà ni yóo sì gbà jáde.”wọ́n sì ṣe ogoji ìtẹ́lẹ̀ fadaka tí wọ́n fi sí abẹ́ ogún àkànpọ̀ igi náà, ìtẹ́lẹ̀ meji meji lábẹ́ àkànpọ̀ igi kọ̀ọ̀kan fún àwọn ìkọ́ rẹ̀ mejeeji. Ẹni tí ó bí ọmọ meje ṣe àárẹ̀, ó sì dákú,oòrùn rẹ̀ wọ̀ lọ́sàn-án gangan.Ìtìjú ati àbùkù bá a.N óo jẹ́ kí ọ̀tá fi idà pa àwọn tí wọ́n kù ninu wọn.Èmi OLUWA ni mo sọ bẹ́ẹ̀.”Nítorí èyí, láti ìgbà tí mo ti gbọ́ nípa igbagbọ yín ninu Oluwa Jesu, ati ìfẹ́ yín sí gbogbo àwọn onigbagbọ, èmi náà Òwò tí a fowó rà, owó la fi ńpa.
Oba nikan ni o le jokoo nibe lati jeun niwaju OLUWA. Yoo gba enu ona iloro wole, ibe naa ni yoo si gba jade.”won si se ogoji itele fadaka ti won fi si abe ogun akanpo igi naa, itele meji meji labe akanpo igi kookan fun awon iko re mejeeji. Eni ti o bi omo meje se aare, o si daku,oorun re wo losan-an gangan.Itiju ati abuku ba a.N oo je ki ota fi ida pa awon ti won ku ninu won.Emi OLUWA ni mo so bee.”Nitori eyi, lati igba ti mo ti gbo nipa igbagbo yin ninu Oluwa Jesu, ati ife yin si gbogbo awon onigbagbo, emi naa Owo ti a fowo ra, owo la fi npa.
Lẹ́yìn náà, Aaroni kọjú sí àwọn eniyan náà, ó gbé ọwọ́ rẹ̀ sókè, ó sì súre fún wọn. Lẹ́yìn náà, ó sọ̀kalẹ̀ láti ibi tí ó ti ń rú ẹbọ ìmúkúrò ẹ̀ṣẹ̀ ati ẹbọ sísun ati ẹbọ alaafia. Nǹkan díẹ̀ tí olódodo nídára ju ọ̀pọ̀ ọrọ̀ àwọn eniyan burúkú.The sun does not beat you, the rain does not beat you, and yet you say you are engaged in a gainful pursuit.
Leyin naa, Aaroni koju si awon eniyan naa, o gbe owo re soke, o si sure fun won. Leyin naa, o sokale lati ibi ti o ti n ru ebo imukuro ese ati ebo sisun ati ebo alaafia. Nnkan die ti olododo nidara ju opo oro awon eniyan buruku.The sun does not beat you, the rain does not beat you, and yet you say you are engaged in a gainful pursuit.
Bákan náà ni ó kọ́ ekeji ati ẹkẹta ati gbogbo àwọn iranṣẹ tí wọ́n tẹ̀lé àwọn agbo ẹran náà. Ó ní, “Nǹkan kan náà ni kí ẹ máa wí fún Esau, nígbà tí ẹ bá pàdé rẹ̀. Ǹjẹ́ a lè gba ìkógun lọ́wọ́ alágbára,tabi kí á gba òǹdè lọ́wọ́ òkúrorò eniyan?Ikekere (type of fish) is treating a deadly thing as something to laugh about.
Bakan naa ni o ko ekeji ati eketa ati gbogbo awon iranse ti won tele awon agbo eran naa. O ni, “Nnkan kan naa ni ki e maa wi fun Esau, nigba ti e ba pade re. Nje a le gba ikogun lowo alagbara,tabi ki a gba onde lowo okuroro eniyan?Ikekere (type of fish) is treating a deadly thing as something to laugh about.
Ẹni à bá tà ká fowó-o rẹ̀ ra àtùpà: ó ní òun à-jí-tanná-wò-lóru.
Eni a ba ta ka fowo-o re ra atupa: o ni oun a-ji-tanna-wo-loru.
Kí alufaa yẹ̀ ẹ́ wò, bí wúwú tí ó wú yìí bá jìn ju awọ ara rẹ̀ lọ, tí irun rẹ̀ bá sì funfun; kí alufaa pè é ní aláìmọ́; àrùn ẹ̀tẹ̀ ni, ẹ̀tẹ̀ ni ó jẹ jáde gẹ́gẹ́ bí oówo. Nígbà tí Angẹli OLUWA sọ ọ̀rọ̀ yìí fún gbogbo àwọn ọmọ Israẹli, wọ́n bẹ̀rẹ̀ sí sọkún tẹ̀dùntẹ̀dùn. Wọ́n lọ káàkiri gbogbo ilẹ̀ Juda pẹlu ìwé òfin lọ́wọ́ wọn, wọ́n ń kọ́ àwọn eniyan.Wọ́n waasu ìyìn rere ní ìlú náà, àwọn eniyan pupọ sì di onigbagbọ. Wọ́n bá pada sí Listira ati Ikoniomu ati Antioku ní Pisidia. Bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé o mọ̀ pé n kò lẹ́bi,ati pé kò sí ẹnikẹ́nití ó lè gbà mí lọ́wọ́ rẹ. A person says he has lost an unspecified amount of money, and you ask if the amount is five hundred cowries or eleven hundred cowries; which amount did you steal?
Ki alufaa ye e wo, bi wuwu ti o wu yii ba jin ju awo ara re lo, ti irun re ba si funfun; ki alufaa pe e ni alaimo; arun ete ni, ete ni o je jade gege bi oowo. Nigba ti Angeli OLUWA so oro yii fun gbogbo awon omo Israeli, won bere si sokun teduntedun. Won lo kaakiri gbogbo ile Juda pelu iwe ofin lowo won, won n ko awon eniyan.Won waasu iyin rere ni ilu naa, awon eniyan pupo si di onigbagbo. Won ba pada si Listira ati Ikoniomu ati Antioku ni Pisidia. Bi o tile je pe o mo pe n ko lebi,ati pe ko si enikeniti o le gba mi lowo re. A person says he has lost an unspecified amount of money, and you ask if the amount is five hundred cowries or eleven hundred cowries; which amount did you steal?
Nítorí n óo rú ọpọlọpọ orílẹ̀-èdè sókè, láti ìhà àríwá, n óo sì kó wọn wá, wọn óo wá dóti Babiloni, wọn yóo gbógun tì í. Ibẹ̀ ni ọwọ́ wọn yóo ti tẹ̀ ẹ́, tí wọn óo sì fogun kó o. Ọfà wọn dàbí akọni ọmọ ogun, tí kì í pada sílé lọ́wọ́ òfo. ṣugbọn Kalebu ọmọ Jefune ni wọ́n fún ní ìgbèríko ati ìletò tí ó yí ìlú Heburoni ká. OLUWA, gbogbo ohun tí o dá ni yóo máa dúpẹ́ lọ́wọ́ rẹ,àwọn eniyan mímọ́ rẹ yóo sì máa yìn ọ́.Ẹlẹ́ẹ̀ẹ́dẹ́ ńlọ ẹ̀ẹ́dẹ́, o ní “Ẹ̀ẹ́dẹ́gbẹ̀ta ni àbí ẹ̀ẹ́dẹ́gbẹ̀fà?”; èwo lo gbé níbẹ̀?
Nitori n oo ru opolopo orile-ede soke, lati iha ariwa, n oo si ko won wa, won oo wa doti Babiloni, won yoo gbogun ti i. Ibe ni owo won yoo ti te e, ti won oo si fogun ko o. Ofa won dabi akoni omo ogun, ti ki i pada sile lowo ofo. sugbon Kalebu omo Jefune ni won fun ni igberiko ati ileto ti o yi ilu Heburoni ka. OLUWA, gbogbo ohun ti o da ni yoo maa dupe lowo re,awon eniyan mimo re yoo si maa yin o.Eleeede nlo eede, o ni “Eedegbeta ni abi eedegbefa?”; ewo lo gbe nibe?
ó ní: “Ìwọ ọmọ eniyan, ǹjẹ́ àwọn ọmọ Israẹli, àwọn ọlọ̀tẹ̀ wọnyi kò bèèrè lọ́wọ́ rẹ pé kí ni ò ń ṣe? Baruku, ọmọ Neraya, ni ó fẹ́ mú wa kọlù ọ́, kí o lè fà wá lé àwọn ará Kalidea lọ́wọ́, kí wọ́n lè pa wá; tabi kí wọ́n kó wa lọ sí ìgbèkùn ní Babiloni.” Jakọbu tún ń bá ìrìn àjò rẹ̀ lọ, nígbà tí ó ṣe, ó dé ilẹ̀ àwọn ará ìlà oòrùn. Nígbà tí ó bá di ọjọ́ keje, kí alufaa yẹ àrùn ẹ̀yi náà wò, tí àrùn náà kò bá tàn káàkiri sí i, tí kò sì jìn ju awọ ara lọ, kí alufaa pè é ní mímọ́, kí ó fọ aṣọ rẹ̀, kí ó sì di mímọ́. A person who should be sold for money to purchase a lamp boasts that he is one-people-light-lamps-to-admire-at-night.
o ni: “Iwo omo eniyan, nje awon omo Israeli, awon olote wonyi ko beere lowo re pe ki ni o n se? Baruku, omo Neraya, ni o fe mu wa kolu o, ki o le fa wa le awon ara Kalidea lowo, ki won le pa wa; tabi ki won ko wa lo si igbekun ni Babiloni.” Jakobu tun n ba irin ajo re lo, nigba ti o se, o de ile awon ara ila oorun. Nigba ti o ba di ojo keje, ki alufaa ye arun eyi naa wo, ti arun naa ko ba tan kaakiri si i, ti ko si jin ju awo ara lo, ki alufaa pe e ni mimo, ki o fo aso re, ki o si di mimo. A person who should be sold for money to purchase a lamp boasts that he is one-people-light-lamps-to-admire-at-night.
Ọlọrun kì í ṣe Ọlọrun àwọn òkú, ti àwọn alààyè ni; nítorí pé gbogbo wọn ni ó wà láàyè fún Ọlọrun.”ọmọ Etani, ọmọ Sima, ọmọ Ṣimei, Ṣugbọn ìwọ pẹlu àwọn ọmọ rẹ nìkan ni alufaa ti yóo máa ṣiṣẹ́ níbi pẹpẹ ìrúbọ ati níbi aṣọ ìbòjú. Èyí ni yóo jẹ́ iṣẹ́ yín nítorí ẹ̀bùn ni mo fi iṣẹ́ alufaa ṣe fun yín. Ẹnikẹ́ni tí ó bá súnmọ́ àwọn ohun mímọ́ yóo kú.”‘OLUWA sọ fún Oluwa mi pé:Jókòó ní ọwọ́ ọ̀tún mitítí n óo fi sọ àwọn ọ̀tá rẹ di ohun ìtìsẹ̀ rẹ.’ Nítorí òtítọ́ ni ọ̀rọ̀ mi;ẹni tí ìmọ̀ rẹ̀ péye ni èmi tí mò ń bá ọ sọ̀rọ̀ yìí.Orí ńlá kì í pá tán.
Olorun ki i se Olorun awon oku, ti awon alaaye ni; nitori pe gbogbo won ni o wa laaye fun Olorun.”omo Etani, omo Sima, omo Simei, Sugbon iwo pelu awon omo re nikan ni alufaa ti yoo maa sise nibi pepe irubo ati nibi aso iboju. Eyi ni yoo je ise yin nitori ebun ni mo fi ise alufaa se fun yin. Enikeni ti o ba sunmo awon ohun mimo yoo ku.”‘OLUWA so fun Oluwa mi pe:Jokoo ni owo otun mititi n oo fi so awon ota re di ohun itise re.’ Nitori otito ni oro mi;eni ti imo re peye ni emi ti mo n ba o soro yii.Ori nla ki i pa tan.
Nígbà náà ni àwọn ọ̀tá mi yóo rí i, ojú yóo sì ti ẹni tí ń pẹ̀gàn mi pé, níbo ni OLUWA Ọlọrun mi wà? N óo fi ojú mi rí i; òun náà yóo wá di àtẹ̀mọ́lẹ̀ bí ẹrẹ̀ ní ìta gbangba.Àwọn ọmọ Reubẹni ati àwọn ọmọ Gadi ni mo sì fún ní agbègbè Gileadi títí dé àfonífojì Anoni, ààrin gbùngbùn àfonífojì náà ni ààlà ilẹ̀ wọn, títí lọ kan odò Jaboku, tíí ṣe ààlà àwọn ará Amoni; akọ mààlúù kékeré kan, àgbò kan, ọ̀dọ́ àgbò kan ọlọ́dún kan fún ẹbọ sísun; Kí ẹnìkọ̀ọ̀kan yín mọ ọ̀nà láti máa bá aya rẹ̀ gbé pọ̀ pẹlu ìwà mímọ́ ati iyì, Mo mọ èyí, ó sì dá mi lójú nípa àṣẹ Oluwa Jesu pé kò sí ohunkohun tí ó jẹ́ èèwọ̀ ní jíjẹ fún ara rẹ̀. Ṣugbọn tí ẹnìkan bá ka nǹkan sí èèwọ̀, èèwọ̀ ni fún irú ẹni bẹ́ẹ̀. Obinrin náà wí fún ọba pé, “Kabiyesi, gbogbo ohun tí o bá ṣe nípa ọ̀rọ̀ yìí, èmi ati ìdílé mi ni a ni ẹ̀bi rẹ̀, ẹ̀bi rẹ̀ kò kan kabiyesi ati ìdílé rẹ̀ rárá.”45. (A rán wọn) pẹ̀lú àwọn Àmì tí
Nigba naa ni awon ota mi yoo ri i, oju yoo si ti eni ti n pegan mi pe, nibo ni OLUWA Olorun mi wa? N oo fi oju mi ri i; oun naa yoo wa di atemole bi ere ni ita gbangba.Awon omo Reubeni ati awon omo Gadi ni mo si fun ni agbegbe Gileadi titi de afonifoji Anoni, aarin gbungbun afonifoji naa ni aala ile won, titi lo kan odo Jaboku, tii se aala awon ara Amoni; ako maaluu kekere kan, agbo kan, odo agbo kan olodun kan fun ebo sisun; Ki enikookan yin mo ona lati maa ba aya re gbe po pelu iwa mimo ati iyi, Mo mo eyi, o si da mi loju nipa ase Oluwa Jesu pe ko si ohunkohun ti o je eewo ni jije fun ara re. Sugbon ti enikan ba ka nnkan si eewo, eewo ni fun iru eni bee. Obinrin naa wi fun oba pe, “Kabiyesi, gbogbo ohun ti o ba se nipa oro yii, emi ati idile mi ni a ni ebi re, ebi re ko kan kabiyesi ati idile re rara.”45. (A ran won) pelu awon Ami ti
ô hàn gbangba àti àwọn Ìwé
o han gbangba ati awon Iwe
Mímọ... Bákan náà ni A sọ ìrántí
Mimo... Bakan naa ni A so iranti
kalẹ̀ fún ọ, kí o lẹ̀ ṣàlàyé fún àwọn
kale fun o, ki o le salaye fun awon
ẹ̀nìyàn nípa ohun tí a sọ kalẹ̀ fún
eniyan nipa ohun ti a so kale fun
wọn, àti pẹ̀ kí wọn lẹ̀ máa ronú.
won, ati pe ki won le maa ronu.
46. Njẹ àwọn tò fì pẹ̀té búburú ní
46. Nje awon to fi pete buburu ni
ìfàyàbalẹ̀ pé Allah kò ní jé kí ilẹ̀
ifayabale pe Allah ko ni je ki ile
gbé wọn mì, tàbí pé ìyà kò ní dé
gbe won mi, tabi pe iya ko ni de
wa bá wọn láti ibi tí wọn kò lérò?
wa ba won lati ibi ti won ko lero?
47. Tàbí pé Òun kò ní gbá wọn
47. Tabi pe Oun ko ni gba won
mú lérí lílọbíbò wọn kí wọn má
mu leri lilobibo won ki won ma
lẹ̀ dojú (àwọn ẹ̀tò Ọlọrun) bolẹ̀?
le doju (awon eto Olorun) bole?
48. Tàbí pé Òun kò ní gbá wọn
48. Tabi pe Oun ko ni gba won
mú pẹ̀lú ìparun diíẹ̀díẹ̀? Dájúdájú
mu pelu iparun diiedie? Dajudaju
Olúwa yín jẹ Aláàánú, Oníkẹ̀ẹ.
Oluwa yin je Alaaanu, Onikee.
49, Ṣe wọn kò ri pé òjìji gbogbo
49, Se won ko ri pe ojiji gbogbo
nùkan tí Allah dá n tẹ̀ sí apá ọtún
nukan ti Allah da n te si apa otun
àti si apá òsì, ní ìtẹríba fún Allah
ati si apa osi, ni iteriba fun Allah
nígbà tí wọn fi ara wọn sí ipò
nigba ti won fi ara won si ipo
ìrẹ̀lẹ̀?
irele?
50. Àti pé ohun gbogbo tí n bẹ ní
50. Ati pe ohun gbogbo ti n be ni
àwọn ọrun àti gbogbo ẹ̀dá tí n bẹ
awon orun ati gbogbo eda ti n be
ní ayé n tẹríbba fún Allah
ni aye n teribba fun Allah
(náà), bẹ̀ ni wọn kì i ṣe
(naa), be ni won ki i se
ìgberaga.
igberaga.
SI. Wọn n bẹ̀rù Olúwa wọn láti
SI. Won n beru Oluwa won lati
òkẹ̀, wọn a sì máa ṣe ohun tí a bá
oke, won a si maa se ohun ti a ba
pa láṣẹ fún wọn.
pa lase fun won.
Ọwọ́ ta ni OLUWA ti gba ìmọ̀ràn tí ó fi ní òye,ta ló kọ́ ọ bí wọ́n ṣe ń dájọ́ ẹ̀tọ́,tí ó kọ́ ọ ní ìmọ̀,tí ó sì fi ọ̀nà òye hàn án?Bí òru bí òru ní ńṣe aláṣọdúdú.
Owo ta ni OLUWA ti gba imoran ti o fi ni oye,ta lo ko o bi won se n dajo eto,ti o ko o ni imo,ti o si fi ona oye han an?Bi oru bi oru ni nse alasodudu.
Àwọn àkànpọ̀ igi tí wọ́n wà ní igun kinni-keji jẹ́ mẹjọ pẹlu ìtẹ́lẹ̀ fadaka mẹrindinlogun, ìtẹ́lẹ̀ meji meji wà lábẹ́ àkànpọ̀ igi kọ̀ọ̀kan.OLUWA bá dá Mose lóhùn pé, It is not in the presence of the flame that water-yam grows hair.
Awon akanpo igi ti won wa ni igun kinni-keji je mejo pelu itele fadaka merindinlogun, itele meji meji wa labe akanpo igi kookan.OLUWA ba da Mose lohun pe, It is not in the presence of the flame that water-yam grows hair.
One dares not strut when one's bane is around. Compare Oju àwòdì kí ladìẹ . . .
One dares not strut when one's bane is around. Compare Oju awodi ki ladie . . .
OLUWA àwọn ọmọ ogun tí ó gbìn ọ́, ti ṣe ìdájọ́ ibi fún ọ, nítorí iṣẹ́ ibi tí ẹ ṣe, ẹ̀yin ilé Israẹli ati ilé Juda; ẹ mú mi bínú nítorí pé ẹ sun turari sí oriṣa Baali.”“Nítorí náà, sọ fún Dafidi iranṣẹ mi pé, ‘Èmi OLUWA àwọn ọmọ ogun ni mo mú un kúrò níbi tí ó ti ń ṣọ́ àwọn aguntan, ninu pápá, mo sì fi jọba Israẹli, àwọn eniyan mi. wọ́n dà á sílẹ̀ níwájú àwọn aposteli kí wọ́n lè pín in fún àwọn tí ó bá ṣe aláìní.“Ẹ tọ Ọlọrun lọ fún èmi ati àwọn eniyan tí wọ́n kù ní Juda ati ní Israẹli, ẹ ṣe ìwádìí ohun tí a kọ sinu ìwé náà; nítorí pé àwọn baba ńlá wa tàpá sí ọ̀rọ̀ OLUWA, wọn kò sì ṣe ohun tí a kọ sinu ìwé yìí ni OLUWA ṣe bínú sí wa lọpọlọpọ.”Ṣugbọn mo mọ̀ pé ìwọ ati àwọn ẹmẹ̀wà rẹ kò bẹ̀rù OLUWA Ọlọrun.”“Wò ó! Nígbà tó bá yá, tí mo bá dá ire Juda ati ti Jerusalẹmu pada,Ìre tí ó sú fún ẹ̀yà Gadi ni pé:“Ibukun ni fún ẹni tí ó bukun ilẹ̀ Gadi,Gadi dàbí kinniun tí ó ba láti fani lápá ya, ati láti géni lórí.“Ìwọ ọmọ eniyan, wò ó! Mo ṣetán tí n óo gba ohun tí ń dùn ọ́ ninu lọ́wọ́ rẹ. Lójijì ni n óo gbà á, o kò sì gbọdọ̀ banújẹ́ tabi kí o sọkún, bẹ́ẹ̀ ni omi kò gbọdọ̀ kán sílẹ̀ lójú rẹ. Obinrin kan bá gbé ọmọ ọlọ kan, ó sọ ọ́ sílẹ̀, ọmọ ọlọ yìí bá Abimeleki lórí, ó sì fọ́ agbárí rẹ̀. Ó yẹ ẹni gbogbo kó dínwó aró, kò yẹ atọ̀ọ́lé.
OLUWA awon omo ogun ti o gbin o, ti se idajo ibi fun o, nitori ise ibi ti e se, eyin ile Israeli ati ile Juda; e mu mi binu nitori pe e sun turari si orisa Baali.”“Nitori naa, so fun Dafidi iranse mi pe, ‘Emi OLUWA awon omo ogun ni mo mu un kuro nibi ti o ti n so awon aguntan, ninu papa, mo si fi joba Israeli, awon eniyan mi. won da a sile niwaju awon aposteli ki won le pin in fun awon ti o ba se alaini.“E to Olorun lo fun emi ati awon eniyan ti won ku ni Juda ati ni Israeli, e se iwadii ohun ti a ko sinu iwe naa; nitori pe awon baba nla wa tapa si oro OLUWA, won ko si se ohun ti a ko sinu iwe yii ni OLUWA se binu si wa lopolopo.”Sugbon mo mo pe iwo ati awon emewa re ko beru OLUWA Olorun.”“Wo o! Nigba to ba ya, ti mo ba da ire Juda ati ti Jerusalemu pada,Ire ti o su fun eya Gadi ni pe:“Ibukun ni fun eni ti o bukun ile Gadi,Gadi dabi kinniun ti o ba lati fani lapa ya, ati lati geni lori.“Iwo omo eniyan, wo o! Mo setan ti n oo gba ohun ti n dun o ninu lowo re. Lojiji ni n oo gba a, o ko si gbodo banuje tabi ki o sokun, bee ni omi ko gbodo kan sile loju re. Obinrin kan ba gbe omo olo kan, o so o sile, omo olo yii ba Abimeleki lori, o si fo agbari re. O ye eni gbogbo ko dinwo aro, ko ye atoole.
Ṣugbọn àwọn ọmọ-ẹ̀yìn yòókù ń bọ̀ ninu ọkọ̀, nítorí wọn kò jìnnà sí èbúté, wọn kò jù bí ìwọ̀n ọgọrun-un ìgbésẹ̀ lọ. Ìdí tí ó fi ṣe èyí ni pé, ó fẹ́ràn àwọn baba ńlá yín, ó sì yan ẹ̀yin tí ẹ jẹ́ ọmọ ọmọ wọn; ó fi agbára ko yín jáde láti ilẹ̀ Ijipti, ó sì wà pẹlu yín. If one engages secretly in treachery, secret disasters befall one.
Sugbon awon omo-eyin yooku n bo ninu oko, nitori won ko jinna si ebute, won ko ju bi iwon ogorun-un igbese lo. Idi ti o fi se eyi ni pe, o feran awon baba nla yin, o si yan eyin ti e je omo omo won; o fi agbara ko yin jade lati ile Ijipti, o si wa pelu yin. If one engages secretly in treachery, secret disasters befall one.
Nígbà náà ni mo bi angẹli náà pé, “OLUWA mi, Kí ni ìtumọ̀ àwọn kinní wọnyi?”tí mo jẹ́ ikọ̀ fún, bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé wọ́n fi ẹ̀wọ̀n dè mí. Ẹ gbadura pé kí n lè fi ìgboyà sọ̀rọ̀ bí ó ti yẹ.Ṣugbọn ẹ ṣọ́ra kí òmìnira yín má di ohun tí yóo gbé àwọn aláìlera ṣubú. Wọ́n sì ṣe aadọta ìkọ́ idẹ láti fi mú aṣọ àgọ́ náà papọ̀ kí ó lè di ẹyọ kan ṣoṣo. Ẹ̀dá tí kò ní olórí, tabi alabojuto, tabi aláṣẹÓ yan àwọn mẹta láti máa ṣe àbojútó gbogbo wọn, Daniẹli sì jẹ́ ọ̀kan ninu wọn. Àwọn mẹta wọnyi ni àwọn ọgọfa (120) gomina náà yóo máa jábọ̀ fún. Àwọn kan bá lọ sọ fún ọba Jẹriko pé, “Àwọn ọkunrin kan, lára àwọn ọmọ Israẹli, wá sí ibí ní alẹ́ yìí láti ṣe amí ilẹ̀ yìí.” Wọ́n tọ́jú àwọn òkúta onikisi, wọ́n jó wọn mọ́ ojú ìtẹ́lẹ̀ wúrà, wọ́n kọ orúkọ àwọn ẹ̀yà Israẹli sí ara wọn, bí wọ́n ti máa ń kọ orúkọ sí ara òrùka èdìdì. Ooré pẹ́, aṣiwèrè-é gbàgbé.
Nigba naa ni mo bi angeli naa pe, “OLUWA mi, Ki ni itumo awon kinni wonyi?”ti mo je iko fun, bi o tile je pe won fi ewon de mi. E gbadura pe ki n le fi igboya soro bi o ti ye.Sugbon e sora ki ominira yin ma di ohun ti yoo gbe awon alailera subu. Won si se aadota iko ide lati fi mu aso ago naa papo ki o le di eyo kan soso. Eda ti ko ni olori, tabi alabojuto, tabi alaseO yan awon meta lati maa se abojuto gbogbo won, Danieli si je okan ninu won. Awon meta wonyi ni awon ogofa (120) gomina naa yoo maa jabo fun. Awon kan ba lo so fun oba Jeriko pe, “Awon okunrin kan, lara awon omo Israeli, wa si ibi ni ale yii lati se ami ile yii.” Won toju awon okuta onikisi, won jo won mo oju itele wura, won ko oruko awon eya Israeli si ara won, bi won ti maa n ko oruko si ara oruka edidi. Oore pe, asiwere-e gbagbe.
mo kórìíra wíwà pẹlu àwọn aṣebi,n kò sì jẹ́ bá àwọn eniyan burúkú da nǹkan pọ̀.OLUWA ní, “Wò ó, níwòyí ọ̀la, n óo da yìnyín bo ilẹ̀, irú èyí tí kò sí ní ilẹ̀ Ijipti rí, láti ọjọ́ tí wọ́n ti tẹ̀ ẹ́ dó títí di òní yìí. Nígbàtí o mọ̀-ọ́ gùn, ẹṣin ẹ-ẹ́ ṣe ṣẹ́ orókún?
mo koriira wiwa pelu awon asebi,n ko si je ba awon eniyan buruku da nnkan po.OLUWA ni, “Wo o, niwoyi ola, n oo da yinyin bo ile, iru eyi ti ko si ni ile Ijipti ri, lati ojo ti won ti te e do titi di oni yii. Nigbati o mo-o gun, esin e-e se se orokun?
kí ó sọ fún àwọn ọmọ Lefi pé, “Nígbà tí ẹ bá gba ìdámẹ́wàá tí OLUWA ti fún yín gẹ́gẹ́ bí ìní yín, ẹ óo san ìdámẹ́wàá ninu rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí ọrẹ fún OLUWA. Joaṣi wà ní ìpamọ́ ninu ilé OLUWA fún ọdún mẹfa, Atalaya sì ń jọba lórí ilẹ̀ Juda.“Ẹ má ṣe jẹ́ kí ọkàn yín dàrú. Ẹ gba Ọlọrun gbọ́, kí ẹ sì gba èmi náà gbọ́. Alufaa yóo mú ninu ìwọ̀n ìgò òróró náà, yóo dà á sí àtẹ́lẹwọ́ òsì rẹ̀. Ilẹ̀ ṣú, ilẹ̀ sì tún mọ́, ó di ọjọ́ kẹta.Wọ́n la ilẹ̀ náà kọjá láti Pega títí wọ́n fi dé ìlú Antioku lẹ́bàá ilẹ̀ Pisidia. Wọ́n lọ sí ilé ìpàdé àwọn Juu ní Ọjọ́ Ìsinmi, wọ́n bá jókòó. Nítorí wọ́n ti ṣe àgbèrè, wọ́n sì ti paniyan; wọ́n ṣe àgbèrè ẹ̀sìn lọ́dọ̀ àwọn oriṣa wọn, wọ́n sì ti pa àwọn ọmọ wọn ọkunrin tí wọ́n bí fún mi, bọ oriṣa wọn. Nígbà tí ó yá, ó rán ẹrú rẹ̀ kan sí àwọn alágbàro náà. Ṣugbọn àwọn alágbàro yìí lù ú, wọ́n bá dá a pada ní ọwọ́ òfo. Ìyàwó ò fọhùn, ó fọ́jú.
ki o so fun awon omo Lefi pe, “Nigba ti e ba gba idamewaa ti OLUWA ti fun yin gege bi ini yin, e oo san idamewaa ninu re gege bi ore fun OLUWA. Joasi wa ni ipamo ninu ile OLUWA fun odun mefa, Atalaya si n joba lori ile Juda.“E ma se je ki okan yin daru. E gba Olorun gbo, ki e si gba emi naa gbo. Alufaa yoo mu ninu iwon igo ororo naa, yoo da a si atelewo osi re. Ile su, ile si tun mo, o di ojo keta.Won la ile naa koja lati Pega titi won fi de ilu Antioku lebaa ile Pisidia. Won lo si ile ipade awon Juu ni Ojo Isinmi, won ba jokoo. Nitori won ti se agbere, won si ti paniyan; won se agbere esin lodo awon orisa won, won si ti pa awon omo won okunrin ti won bi fun mi, bo orisa won. Nigba ti o ya, o ran eru re kan si awon alagbaro naa. Sugbon awon alagbaro yii lu u, won ba da a pada ni owo ofo. Iyawo o fohun, o foju.