diacritcs
stringlengths
1
36.7k
no_diacritcs
stringlengths
1
35.5k
ìṣẹlẹ̀rú máa tú jáde fún wa láti
iseleru maa tu jade fun wa lati
inú ilẹ̀.
inu ile.
92. 'Tàbí kí o ní ọgbà kan tí igi
92. 'Tabi ki o ni ogba kan ti igi
òpẹ àti àjàrà n bẹ nínú rẹ̀, tí ìwọ
ope ati ajara n be ninu re, ti iwo
sì n mú kí àwọn odò náà tú jáde
si n mu ki awon odo naa tu jade
lọpọlọpọ laàrin rẹ̀.
lopolopo laarin re.
93. 'Tàbí kí o jẹ̀ kí ẹ̀run ya
93. 'Tabi ki o je ki erun ya
wẹlẹwẹlẹ bò wá mọlẹ̀, gẹgẹ bí o
welewele bo wa mole, gege bi o
ti ṣe n kéde, tàbí ki o mú Allah
ti se n kede, tabi ki o mu Allah
àti àwọn. Màláíkà wá bá wa
ati awon. Malaika wa ba wa
lojúkorojú.
lojukoroju.
94. 'Tabí kí o ní ilé kan ti oô jẹ ti
94. 'Tabi ki o ni ile kan ti oo je ti
wúrà tàbí kí o gun òkẹ̀ lọ sí ọrun;
wura tabi ki o gun oke lo si orun;
àwa kò sì ní gba ìgòkẹ̀ re ọrun rẹ
awa ko si ni gba igoke re orun re
náà gbọ, àyàfi tí ìwọ bá lò mú
naa gbo, ayafi ti iwo ba lo mu
odidi Ìwé kan tí a lẹ̀ kà
odidi Iwe kan ti a le ka
Filipi ati Batolomiu, Tomasi ati Matiu agbowó-odè, Jakọbu ọmọ Alfeu ati Tadiu. O la ọ̀nà tí ó gbòòrò fún mi,n kò sì fi ẹsẹ̀ rọ́.Gbogbo àwọn eniyan ṣe akiyesi ohun tí ọba ṣe yìí, ó sì dùn mọ́ wọn. Gbogbo ohun tí ọba ṣe patapata ni ó dùn mọ́ àwọn eniyan. Olójúkòkòrò eniyan a máa dá ìjà sílẹ̀,ṣugbọn ẹni tí ó gbẹ́kẹ̀lé OLUWA yóo ṣe rere.Báwo ni Kristi ti ṣe lè fi ohùn ṣọ̀kan pẹlu Èṣù? Kí ni ìbá pa onigbagbọ ati alaigbagbọ pọ̀? àwọn ràkúnmí wọn jẹ́ ojilenirinwo ó dín marun-un (435), àwọn kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ wọn sì jẹ́ ẹgbaata ó lé ọrindinlẹgbẹrin (6,720).Jesu bi í pé, “Kí ni o fẹ́ kí n ṣe fún ọ?”Afọ́jú náà dáhùn pé, “Olùkọ́ni, mo fẹ́ tún ríran ni.”Ẹ bá Jerusalẹmu yọ̀, kí inú yín dùn nítorí rẹ̀,gbogbo ẹ̀yin tí ẹ fẹ́ràn rẹ̀,ẹ bá a yọ̀ ṣẹ̀ṣẹ̀,gbogbo ẹ̀yin tí ẹ̀ ń ṣọ̀fọ̀ nítorí rẹ̀.Ṣugbọn ó sọ fún wọn pé, “Kì í ṣe gbogbo eniyan ni ó lè gba nǹkan yìí, àfi àwọn tí Ọlọrun bá fi fún láti gbà á. 9, Àwa yòò sì sọ gbogbo ohun tú
Filipi ati Batolomiu, Tomasi ati Matiu agbowo-ode, Jakobu omo Alfeu ati Tadiu. O la ona ti o gbooro fun mi,n ko si fi ese ro.Gbogbo awon eniyan se akiyesi ohun ti oba se yii, o si dun mo won. Gbogbo ohun ti oba se patapata ni o dun mo awon eniyan. Olojukokoro eniyan a maa da ija sile,sugbon eni ti o gbekele OLUWA yoo se rere.Bawo ni Kristi ti se le fi ohun sokan pelu Esu? Ki ni iba pa onigbagbo ati alaigbagbo po? awon rakunmi won je ojilenirinwo o din marun-un (435), awon ketekete won si je egbaata o le orindinlegberin (6,720).Jesu bi i pe, “Ki ni o fe ki n se fun o?”Afoju naa dahun pe, “Olukoni, mo fe tun riran ni.”E ba Jerusalemu yo, ki inu yin dun nitori re,gbogbo eyin ti e feran re,e ba a yo sese,gbogbo eyin ti e n sofo nitori re.Sugbon o so fun won pe, “Ki i se gbogbo eniyan ni o le gba nnkan yii, afi awon ti Olorun ba fi fun lati gba a. 9, Awa yoo si so gbogbo ohun tu
wà loòrí rẹ̀ di gbígbẹ.
wa loori re di gbigbe.
10. Njẹ ìwọ ha rò pé àwọn ara
10. Nje iwo ha ro pe awon ara
ihò àpáta àti àkọsílẹ̀ j$ ohun
iho apata ati akosile j$ ohun
ìyanu nínú àwọn Amì Wa bí?
iyanu ninu awon Ami Wa bi?
11. Nígbà tí àwọn ọdọmọkùnrin
11. Nigba ti awon odomokunrin
náà sá àsálà fún ààbò sínú ihò
naa sa asala fun aabo sinu iho
àpáta náà, wQn sì n gbàdúrà pé:
apata naa, wQn si n gbadura pe:
Olúwa wa, ṣíjú àánú wò wa lati òdò Rẹ wá kí O sì ṣe amọònà wa sí ònà tí ô tọ nípa àlámòọrí wa.
Oluwa wa, siju aanu wo wa lati odo Re wa ki O si se amoona wa si ona ti o to nipa alamoori wa.
12. Àwa kò jẹ kí etí wọn gbọ òrò
12. Awa ko je ki eti won gbo oro
(láti ìta) nínú ihò náà fún ọdún tí
(lati ita) ninu iho naa fun odun ti
Òô níye.
Oo niye.
13. Lẹ̀hìn náà, A gbé wọn dìde kí
13. Lehin naa, A gbe won dide ki
A lẹ̀ baà mọ òwo nínú ìjọ méjẹòjì
A le baa mo owo ninu ijo mejeoji
tí yoòò le sọ òpin ìgbà tí wọn lò
ti yooo le so opin igba ti won lo
(nínú ihò náà).
(ninu iho naa).
ÌDÁ 2
IDA 2
14. Àwa nì sọ ìtàn wọn fún ọ pẹ̀lú
14. Awa ni so itan won fun o pelu
òdodo... Dájúdájú wQn... jẹ
ododo... Dajudaju wQn... je
òdọmọkùnrin tí wọn gba Olúwa
odomokunrin ti won gba Oluwa
wọn gbọ lododo. A sì ṣe àlékún
won gbo lododo. A si se alekun
ìtọsọnà fún wọn.
itosona fun won.
15. Àwa sì kì woôn laáyà tagbára-
15. Awa si ki woon laaya tagbara-
tagbara nígbà tí wọn dìde dúrú ti
tagbara nigba ti won dide duru ti
wọn sì n wí pé, 'Olúwa wa ni
won si n wi pe, 'Oluwa wa ni
Ohúwa àti ayé, àwa kò ní ké
Ohuwa ati aye, awa ko ni ke
pe Ọlọrun mìíràn lẹhìn Rẹ̀, bí a
pe Olorun miiran lehin Re, bi a
bá wá ṣe bẹ̀ẹ̀, dájúdájú a ti sọ ẹrọ
ba wa se bee, dajudaju a ti so ero
ti 0 lòdì sí òtítọ (si ìjọkan ṣoṣo
ti 0 lodi si otito (si ijokan soso
Dafidi sì wà ninu ìbànújẹ́, nítorí pé inú àwọn ọmọlẹ́yìn rẹ̀ bàjẹ́ nítorí àwọn ọmọ wọn, wọ́n sì ń gbèrò láti sọ ọ́ ní òkúta pa. Ṣugbọn Dafidi túbọ̀ ní igbẹkẹle ninu OLUWA Ọlọrun rẹ̀. Samuẹli bá wí fún àwọn eniyan náà pé, “Ẹni tí OLUWA yàn nìyí. Kò sí ẹnikẹ́ni láàrin wa tí ó dàbí rẹ̀.”Gbogbo àwọn eniyan náà kígbe sókè pé, “Kí ọba kí ó pẹ́.”Nítorí pé gbogbo òfin rẹ̀ ni mo tẹ̀lé,n kò sì yà kúrò ninu ìlànà rẹ̀.OLUWA, níbo ni ìfẹ́ rẹ ìgbàanì tí kì í yẹ̀ wà,tí o búra fún Dafidi pẹlu òtítọ́ rẹ?Bákan náà, wọ́n kó àwọn àwo ìfọnná, ati àwọn àwo kòtò, gbogbo ohun tí ó jẹ́ ti wúrà ati fadaka, ni olórí àwọn tí wọn ń ṣọ́ ọba Babiloni kó lọ. Àwọn mààlúù tí wọ́n rù wọnyi gbé àwọn tí wọ́n sanra mì. Heṣiboni ati Jaseri, pẹlu àwọn pápá oko àyíká wọn.Ó kìlọ̀ fún wọn ó ní, “Ẹ ṣọ́ra gan-an, nítorí pé kì í ṣe eniyan ni ẹ̀ ń ṣiṣẹ́ fún, OLUWA ni. Ẹ sì ranti pé OLUWA wà lọ́dọ̀ yín bí ẹ ti ń ṣe ìdájọ́. Ọgbọ́n àgbọ́njù ní ńpa òdù ọ̀yà.
Dafidi si wa ninu ibanuje, nitori pe inu awon omoleyin re baje nitori awon omo won, won si n gbero lati so o ni okuta pa. Sugbon Dafidi tubo ni igbekele ninu OLUWA Olorun re. Samueli ba wi fun awon eniyan naa pe, “Eni ti OLUWA yan niyi. Ko si enikeni laarin wa ti o dabi re.”Gbogbo awon eniyan naa kigbe soke pe, “Ki oba ki o pe.”Nitori pe gbogbo ofin re ni mo tele,n ko si ya kuro ninu ilana re.OLUWA, nibo ni ife re igbaani ti ki i ye wa,ti o bura fun Dafidi pelu otito re?Bakan naa, won ko awon awo ifonna, ati awon awo koto, gbogbo ohun ti o je ti wura ati fadaka, ni olori awon ti won n so oba Babiloni ko lo. Awon maaluu ti won ru wonyi gbe awon ti won sanra mi. Hesiboni ati Jaseri, pelu awon papa oko ayika won.O kilo fun won o ni, “E sora gan-an, nitori pe ki i se eniyan ni e n sise fun, OLUWA ni. E si ranti pe OLUWA wa lodo yin bi e ti n se idajo. Ogbon agbonju ni npa odu oya.
Ò máa ran àwọn tí ń fi inú dídùn ṣiṣẹ́ òdodo lọ́wọ́,àwọn tí wọn ranti rẹ ninu ìgbé ayé wọn,o bínú, nítorí náà a dẹ́ṣẹ̀,a ti wà ninu ẹ̀ṣẹ̀ wa tipẹ́.Ǹjẹ́ a óo rí ìgbàlà?Bí Jeremaya wolii ti dé bodè Bẹnjamini ọ̀kan ninu àwọn oníbodè tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ Irija ọmọ Ṣelemaya ọmọ Hananaya mú un, ó ní, “O fẹ́ sálọ bá àwọn ará Kalidea ni.”Nítorí Ọlọrun fẹ́ aráyé tóbẹ́ẹ̀ tí ó fi Ọmọ bíbí rẹ̀ kanṣoṣo fúnni, pé kí ẹnikẹ́ni tí ó bá gbà á gbọ́ má baà ṣègbé, ṣugbọn kí ó lè ní ìyè ainipẹkun. Ṣekemu bá lọ sọ fún Hamori, baba rẹ̀, pé kí ó fẹ́ ọmọbinrin náà fún òun.Ní ọjọ́ keje, wọ́n gbéra ní òwúrọ̀ kutukutu, wọ́n yípo ìlú náà bí wọ́n ti máa ń ṣe, nígbà meje. Ọjọ́ keje yìí nìkan ṣoṣo ni wọ́n yípo rẹ̀ lẹẹmeje. Paulu ati Banaba pẹ́ níbẹ̀. Wọ́n ń sọ̀rọ̀ ní gbangba, ẹ̀rù kò sì bà wọ́n nítorí wọ́n gbójú lé Oluwa tí ó jẹ́rìí sí ọ̀rọ̀ oore-ọ̀fẹ́ rẹ̀ nípa iṣẹ́ abàmì ati iṣẹ́ ìyanu tí ó ń ti ọwọ́ wọn ṣe. Jerusalẹmu ti dẹ́ṣẹ̀ burúkú,nítorí náà ó ti di eléèérí.Àwọn tí wọn ń bu ọlá fún un tẹ́lẹ̀ ti ń kẹ́gàn rẹ̀,nítorí pé wọ́n ti rí ìhòòhò rẹ̀.Òun pàápàá ń kérora, ó sì fi ojú pamọ́.Josẹfu bọ́ sinu kẹ̀kẹ́ ẹlẹ́ṣin rẹ̀, ó lọ pàdé Israẹli, baba rẹ̀ ní Goṣeni. Nígbà tí Josẹfu dé ọ̀dọ̀ baba rẹ̀, ó rọ̀ mọ́ ọn lọ́rùn, ó sì sọkún fún ìgbà pípẹ́. Bí wọn bá ń lọ àwọn àgbá náà a máa yí lọ pẹlu wọn. Bí wọ́n bá dúró àwọn àgbá náà a dúró. Bí wọn bá gbéra nílẹ̀, àwọn àgbá náà a gbéra nílẹ̀, nítorí pé ninu àwọn àgbá wọnyi ni ẹ̀mí àwọn ẹ̀dá alààyè náà wà. sọ pé, "Ẹyin kò ha mò pé,
O maa ran awon ti n fi inu didun sise ododo lowo,awon ti won ranti re ninu igbe aye won,o binu, nitori naa a dese,a ti wa ninu ese wa tipe.Nje a oo ri igbala?Bi Jeremaya wolii ti de bode Benjamini okan ninu awon onibode ti oruko re n je Irija omo Selemaya omo Hananaya mu un, o ni, “O fe salo ba awon ara Kalidea ni.”Nitori Olorun fe araye tobee ti o fi Omo bibi re kansoso funni, pe ki enikeni ti o ba gba a gbo ma baa segbe, sugbon ki o le ni iye ainipekun. Sekemu ba lo so fun Hamori, baba re, pe ki o fe omobinrin naa fun oun.Ni ojo keje, won gbera ni owuro kutukutu, won yipo ilu naa bi won ti maa n se, nigba meje. Ojo keje yii nikan soso ni won yipo re leemeje. Paulu ati Banaba pe nibe. Won n soro ni gbangba, eru ko si ba won nitori won gboju le Oluwa ti o jerii si oro oore-ofe re nipa ise abami ati ise iyanu ti o n ti owo won se. Jerusalemu ti dese buruku,nitori naa o ti di eleeeri.Awon ti won n bu ola fun un tele ti n kegan re,nitori pe won ti ri ihooho re.Oun paapaa n kerora, o si fi oju pamo.Josefu bo sinu keke elesin re, o lo pade Israeli, baba re ni Goseni. Nigba ti Josefu de odo baba re, o ro mo on lorun, o si sokun fun igba pipe. Bi won ba n lo awon agba naa a maa yi lo pelu won. Bi won ba duro awon agba naa a duro. Bi won ba gbera nile, awon agba naa a gbera nile, nitori pe ninu awon agba wonyi ni emi awon eda alaaye naa wa. so pe, "Eyin ko ha mo pe,
dájúdájú bàbá yín ti gba àdéhùn
dajudaju baba yin ti gba adehun
kan lọwọ yín lòrúkọ Allah, àti bí
kan lowo yin loruko Allah, ati bi
ẹ ti kùnà nípa ojúṣe yín lòrí
e ti kuna nipa ojuse yin lori
Yusuf? Ní ti ẹ̀mi o, ẹ̀mi kò ní
Yusuf? Ni ti emi o, emi ko ni
kúrò ní ìlú yìí títí tí bàbá mi yòôò
kuro ni ilu yii titi ti baba mi yooo
fi fún mi láàyò tàbí tí Allah yúò
fi fun mi laayo tabi ti Allah yuo
fi pinnu fún mi. Òun ni Adájọ tô
fi pinnu fun mi. Oun ni Adajo to
dára jùlọ.
dara julo.
82. "Ẹ padà tọ bàbá yín lọ, kí ẹ sì
82. "E pada to baba yin lo, ki e si
wí pé, "Bàbá wa, dájúdájú ọmọ
wi pe, "Baba wa, dajudaju omo
yin ti jalẹ̀, ohun tí a mọ ni a ti sọ
yin ti jale, ohun ti a mo ni a ti so
yìí, àwa kò sì jẹ olùṣọ ohun tí ô
yii, awa ko si je oluso ohun ti o
pamọ.
pamo.
83. 'Kí ẹ sì ṣe ìwádìí lọdẹò àwọn
83. 'Ki e si se iwadii lodeo awon
ará ìlú tí a wà àti àwọn arìnrìn-
ara ilu ti a wa ati awon arinrin-
àjò tí a jọ rìn, dájúdájú òtítọ ni a
ajo ti a jo rin, dajudaju otito ni a
n sọ."
n so."
84. Ô fẹ̀sì pé, 'Kò jẹ jẹ bẹ̀ẹ̀,
84. O fesi pe, 'Ko je je bee,
ṣùgbọn ẹ̀mí yín ni Ò tàn yín jẹ
sugbon emi yin ni O tan yin je
nípa fifi hàn yín gẹgẹ bí ohun tí ô
nipa fifi han yin gege bi ohun ti o
dára. (nípa bẹ̀) ṣíṣe sùúrù lô dara
dara. (nipa be) sise suuru lo dara
jù. Ô ṣe é ṣe kí Allah mú gbogbo
ju. O se e se ki Allah mu gbogbo
wọn padà wá bá mi; nítorí pé
won pada wa ba mi; nitori pe
Òun ni Olùmọò ohun gbogbo,
Oun ni Olumoo ohun gbogbo,
Ọlọgbọn jùlọ."
Ologbon julo."
85. Ô sì yípadà lọdò wọn, ô wí
85. O si yipada lodo won, o wi
pé; 'Inú mi bàjẹ nítorí ti Yusuf!
pe; 'Inu mi baje nitori ti Yusuf!
Omijé sì kún ojú rẹ̀ fun ìbànújẹ,
Omije si kun oju re fun ibanuje,
ô sì n pa (ìbànújẹ rẹ̀) mọra.
o si n pa (ibanuje re) mora.
86. Wén sọ pé, 'Àwa fi Allah
86. Wen so pe, 'Awa fi Allah
búra pé, ẹ kò ní yé sọ nípa Yusuf
bura pe, e ko ni ye so nipa Yusuf
títí ti ẹ O bẹ̀rẹ̀ sí ṣàìsàn tàbí kí ẹ kú.
titi ti e O bere si saisan tabi ki e ku.
Ṣugbọn kékeré nìyí ninu agbára rẹ̀,díẹ̀ ni a tíì gbọ́ nípa iṣẹ́ rẹ̀!Nítorí náà ta ló lè mọ títóbi agbára rẹ̀?”Judasi ọmọ Jakọbu ati Judasi Iskariotu, ẹni tí ó di ọ̀dàlẹ̀.OLUWA bá dá Mose lóhùn, ó ní, “Tọ àwọn eniyan náà lọ kí o sì yà wọ́n sí mímọ́ lónìí ati lọ́la. Sọ fún wọn pé kí wọ́n fọ aṣọ wọn, kí wọ́n wà ní ìmúrasílẹ̀ ní ọjọ́ kẹta, Nígbà tí mo rò pé, “Ẹsẹ̀ mi ti yọ̀,”OLUWA, ìfẹ́ rẹ tí kì í yẹ̀ ni ó gbé mi ró.“Iná ni mo wá sọ sí ayé. Ìbá ti dùn tó bí ó bá bẹ̀rẹ̀ sí jó! Ìwọ̀n ọ̀kọ̀ọ̀kan ninu àwọn àwo kòtò mejeejila tí wọ́n kún fún turari jẹ́ ṣekeli mẹ́wàá mẹ́wàá. Ìwọ̀n ṣekeli tí wọn ń lò ní ibi mímọ́ ni wọ́n fi wọ̀n wọ́n. Ìwọ̀n àwọn àwo kòtò tí wọ́n fi wúrà ṣe jẹ́ ọgọfa (120) ṣekeli. Wọ́n tẹ́ tabili, wọ́n sì tẹ́ aṣọ sílẹ̀wọ́n ń jẹ, wọ́n ń mu.Ariwo bá ta pé“Ẹ gbéra nílẹ̀, ẹ̀yin ológun!Ẹ fepo pa asà yín.”Ọba sì rán ọkunrin meji pẹlu kẹ̀kẹ́ ogun meji láti lọ wo ohun tí ó ṣẹlẹ̀. Nítorí mo wá láti dá ìyapa sílẹ̀, láàrin ọmọkunrin ati baba rẹ̀, láàrin ọmọbinrin ati ìyá rẹ̀, ati láàrin iyawo ati ìyá ọkọ rẹ̀. Iye àwọn ọmọ Lefi tí ó kó jọ láti inú ìdílé kọ̀ọ̀kan nìwọ̀nyí: láti inú ìdílé Kohati: ọgọfa (120) ọkunrin, Urieli ni olórí wọn; OLUWA, dáríjì Israẹli, àwọn eniyan rẹ, tí o ti rà pada, má sì ṣe jẹ àwọn eniyan Israẹli níyà nítorí ikú aláìṣẹ̀ yìí. Ṣugbọn dárí ẹ̀bi ẹ̀ṣẹ̀ ìtàjẹ̀sílẹ̀ náà jì wọ́n.’ Èrò yín dàbí fùlùfúlù, gbogbo ìṣe yín dàbí pòpórò ọkà.Èémí mi yóo jó yín run bí iná.Òtítọ́ ni ọ̀rọ̀ yìí pé, ‘Ọ̀tọ̀ ni ẹni tí ń fúnrúgbìn, ọ̀tọ̀ ni ẹni tí ń kórè.’ Joṣua dìde ní òwúrọ̀ kutukutu ọjọ́ keji, ó pe gbogbo àwọn eniyan náà jọ. Òun ati àwọn àgbààgbà Israẹli ṣáájú wọn, wọ́n lọ sí Ai. The child of a cripple who bought shoes for his father is asking for a stern lecture.
Sugbon kekere niyi ninu agbara re,die ni a tii gbo nipa ise re!Nitori naa ta lo le mo titobi agbara re?”Judasi omo Jakobu ati Judasi Iskariotu, eni ti o di odale.OLUWA ba da Mose lohun, o ni, “To awon eniyan naa lo ki o si ya won si mimo lonii ati lola. So fun won pe ki won fo aso won, ki won wa ni imurasile ni ojo keta, Nigba ti mo ro pe, “Ese mi ti yo,”OLUWA, ife re ti ki i ye ni o gbe mi ro.“Ina ni mo wa so si aye. Iba ti dun to bi o ba bere si jo! Iwon okookan ninu awon awo koto mejeejila ti won kun fun turari je sekeli mewaa mewaa. Iwon sekeli ti won n lo ni ibi mimo ni won fi won won. Iwon awon awo koto ti won fi wura se je ogofa (120) sekeli. Won te tabili, won si te aso silewon n je, won n mu.Ariwo ba ta pe“E gbera nile, eyin ologun!E fepo pa asa yin.”Oba si ran okunrin meji pelu keke ogun meji lati lo wo ohun ti o sele. Nitori mo wa lati da iyapa sile, laarin omokunrin ati baba re, laarin omobinrin ati iya re, ati laarin iyawo ati iya oko re. Iye awon omo Lefi ti o ko jo lati inu idile kookan niwonyi: lati inu idile Kohati: ogofa (120) okunrin, Urieli ni olori won; OLUWA, dariji Israeli, awon eniyan re, ti o ti ra pada, ma si se je awon eniyan Israeli niya nitori iku alaise yii. Sugbon dari ebi ese itajesile naa ji won.’ Ero yin dabi fulufulu, gbogbo ise yin dabi poporo oka.Eemi mi yoo jo yin run bi ina.Otito ni oro yii pe, ‘Oto ni eni ti n funrugbin, oto ni eni ti n kore.’ Josua dide ni owuro kutukutu ojo keji, o pe gbogbo awon eniyan naa jo. Oun ati awon agbaagba Israeli saaju won, won lo si Ai. The child of a cripple who bought shoes for his father is asking for a stern lecture.
Mose bá tọ àwọn eniyan náà lọ, ó sọ gbogbo ohun tí OLUWA sọ fún un fún wọn, ati gbogbo ìlànà tí ó là sílẹ̀, gbogbo àwọn eniyan náà sì fi ẹnu kò, wọ́n dáhùn pé, “Gbogbo ohun tí OLUWA wí ni a óo ṣe.” Absalomu bí ọmọkunrin mẹta ati ọmọbinrin kan. Tamari ni orúkọ ọmọbinrin yìí, ó sì jẹ́ arẹwà.Ará Dani ni ìyá rẹ̀, ṣugbọn ará Tire ni baba rẹ̀. Ó mọ iṣẹ́ àgbẹ̀dẹ wúrà, ati ti fadaka, ti bàbà, ati ti irin; ó sì mọ òkúta, ati igi í gbẹ́. Ó mọ bí a tií ṣe iṣẹ́ ọnà sí ara aṣọ elése àlùkò, aṣọ aláwọ̀ aró, àlàárì, ati aṣọ ọ̀gbọ̀ onílà tẹ́ẹ́rẹ́tẹ́ẹ́rẹ́. Ó lè ṣe iṣẹ́ gbẹ́nàgbẹ́nà, ó sì lè ṣe oríṣìíríṣìí iṣẹ́ ọnà tí wọ́n bá ní kí ó ṣe pẹlu àwọn òṣìṣẹ́ tìrẹ, ati àwọn òṣìṣẹ́ oluwa mi, Dafidi, baba rẹ. Ọ̀kọ̀ọ̀kan là ńyọ ẹsẹ̀ lábàtà.
Mose ba to awon eniyan naa lo, o so gbogbo ohun ti OLUWA so fun un fun won, ati gbogbo ilana ti o la sile, gbogbo awon eniyan naa si fi enu ko, won dahun pe, “Gbogbo ohun ti OLUWA wi ni a oo se.” Absalomu bi omokunrin meta ati omobinrin kan. Tamari ni oruko omobinrin yii, o si je arewa.Ara Dani ni iya re, sugbon ara Tire ni baba re. O mo ise agbede wura, ati ti fadaka, ti baba, ati ti irin; o si mo okuta, ati igi i gbe. O mo bi a tii se ise ona si ara aso elese aluko, aso alawo aro, alaari, ati aso ogbo onila teereteere. O le se ise gbenagbena, o si le se orisiirisii ise ona ti won ba ni ki o se pelu awon osise tire, ati awon osise oluwa mi, Dafidi, baba re. Okookan la nyo ese labata.
Ọba Sodomu sọ fún Abramu pé, “Jọ̀wọ́, máa kó gbogbo ìkógun lọ, ṣugbọn dá àwọn eniyan mi pada fún mi.”Gbogbo wọn ni wọ́n mu omi ẹ̀mí kan náà, nítorí wọ́n mu omi tí ó jáde láti inú òkúta ẹ̀mí tí ó ń tẹ̀lé wọn. Òkúta náà ni Kristi. Nígbà tí Jehu pada sí ọ̀dọ̀ àwọn ẹgbẹ́ rẹ̀, wọ́n bèèrè lọ́wọ́ rẹ̀ pé, “Ṣé kò sí nǹkan? Kí ni ọkunrin bíi wèrè yìí ń wá lọ́dọ̀ rẹ?”Jehu dáhùn pé, “Ǹjẹ́ ẹ mọ ọkunrin náà, ati ohun tí ó sọ?”Eniyan burúkú a máa lo ògbójú,ṣugbọn olóòótọ́ máa ń yẹ ọ̀nà ara rẹ̀ wò.Lẹsẹkẹsẹ bí Ahabu ti gbọ́ pé Naboti ti kú, ó lọ sí ibi ọgbà àjàrà náà, ó sì gbà á.Nítorí pé ère lásán ni àwọn orílẹ̀-èdè yòókù sọ di ọlọrun,ṣugbọn OLUWA ló dá ọ̀run.Ohunkohun tí ó wà, ó ti wà tẹ́lẹ̀, èyí tí yóo sì tún wà, òun pàápàá ti wà rí; Ọlọrun yóo ṣe ìwádìí gbogbo ohun tí ó ti kọjá.Whoever conceals a disease is beyond help from a doctor.
Oba Sodomu so fun Abramu pe, “Jowo, maa ko gbogbo ikogun lo, sugbon da awon eniyan mi pada fun mi.”Gbogbo won ni won mu omi emi kan naa, nitori won mu omi ti o jade lati inu okuta emi ti o n tele won. Okuta naa ni Kristi. Nigba ti Jehu pada si odo awon egbe re, won beere lowo re pe, “Se ko si nnkan? Ki ni okunrin bii were yii n wa lodo re?”Jehu dahun pe, “Nje e mo okunrin naa, ati ohun ti o so?”Eniyan buruku a maa lo ogboju,sugbon oloooto maa n ye ona ara re wo.Lesekese bi Ahabu ti gbo pe Naboti ti ku, o lo si ibi ogba ajara naa, o si gba a.Nitori pe ere lasan ni awon orile-ede yooku so di olorun,sugbon OLUWA lo da orun.Ohunkohun ti o wa, o ti wa tele, eyi ti yoo si tun wa, oun paapaa ti wa ri; Olorun yoo se iwadii gbogbo ohun ti o ti koja.Whoever conceals a disease is beyond help from a doctor.
Mose bá tẹ́ pẹpẹ kan, ó sì pe orúkọ rẹ̀ ní “OLUWA ni àsíá mi.” Ṣugbọn àwọn kan ninu wọn lọ sọ́dọ̀ àwọn Farisi, wọ́n lọ sọ ohun gbogbo tí Jesu ṣe. Á dí orísun àwọn odò,tóbẹ́ẹ̀ tí wọn kò fi lè sun,á sì wá àwọn ohun tí ó pamọ́ jáde.“Ọmọ ni ẹ jẹ́ fún OLUWA Ọlọrun yín, nítorí náà, ẹ kò gbọdọ̀ fi abẹ ya ara yín lára tabi kí ẹ fá irun yín níwájú nígbà tí ẹ bá ń ṣọ̀fọ̀ ẹni tí ó kú. Àwọn tí ó bọ́ sórí òkúta ni àwọn tí ó gbọ́, tí wọ́n fi tayọ̀tayọ̀ gba ọ̀rọ̀ náà, ṣugbọn wọn kò ní gbòǹgbò. Wọ́n gbàgbọ́ fún àkókò díẹ̀. Ṣugbọn nígbà tí ìdánwò dé, wọ́n bọ́hùn. Nítorí náà, ẹ̀yin àyànfẹ́ mi, gẹ́gẹ́ bí ẹ ti ń gbọ́ràn nígbà gbogbo, tí kì í ṣe nígbà tí mo bá wà lọ́dọ̀ yín nìkan, ṣugbọn pàápàá jùlọ ní àkókò yìí tí n kò sí lọ́dọ̀ yín, ẹ máa ṣe iṣẹ́ ìgbàlà yín pẹlu ìbẹ̀rù ati ìwárìrì. Àwọn ọmọ Paṣuri jẹ́ ẹgbẹfa ó lé mẹtadinlaadọta (1,247). “Ẹ mú ìyẹ̀fun tí ó kúnná dáradára, kí ẹ sì fi ṣe burẹdi mejila, ìdámárùn-ún ìwọ̀n ìyẹ̀fun efa kan ni kí ẹ fi ṣe burẹdi kọ̀ọ̀kan. Nígbà tí wọ́n dé ọ̀dọ̀ àwọn eniyan, ọkunrin kan wá sọ́dọ̀ Jesu, ó kúnlẹ̀ níwájú rẹ̀. Èrò mi lórí ọ̀rọ̀ yìí ni pé ohun tí ó dára jùlọ fun yín ni. Nígbà tí kì í tíí ṣe pé ẹ ti ń ṣe é nìkan ni, ṣugbọn tìfẹ́tìfẹ́ ni ẹ ti fi ń ṣe é láti ọdún tí ó kọjá, Nítorí kò sí ohun tí ó ṣòro fún Ọlọrun.” Láìsí igi, iná óo kú,bẹ́ẹ̀ ni, láìsí olófòófó, ìjà óo tán.Ẹ kíyèsí àwọn ohun tí ń ṣẹlẹ̀ si yín. Èmi OLUWA àwọn ọmọ ogun ni mo sọ bẹ́ẹ̀. It is an insatiable Ṣàngó priest who names his son Bámigbóṣé one should procure for oneself a ritual rod one can carry.
Mose ba te pepe kan, o si pe oruko re ni “OLUWA ni asia mi.” Sugbon awon kan ninu won lo sodo awon Farisi, won lo so ohun gbogbo ti Jesu se. A di orisun awon odo,tobee ti won ko fi le sun,a si wa awon ohun ti o pamo jade.“Omo ni e je fun OLUWA Olorun yin, nitori naa, e ko gbodo fi abe ya ara yin lara tabi ki e fa irun yin niwaju nigba ti e ba n sofo eni ti o ku. Awon ti o bo sori okuta ni awon ti o gbo, ti won fi tayotayo gba oro naa, sugbon won ko ni gbongbo. Won gbagbo fun akoko die. Sugbon nigba ti idanwo de, won bohun. Nitori naa, eyin ayanfe mi, gege bi e ti n gboran nigba gbogbo, ti ki i se nigba ti mo ba wa lodo yin nikan, sugbon paapaa julo ni akoko yii ti n ko si lodo yin, e maa se ise igbala yin pelu iberu ati iwariri. Awon omo Pasuri je egbefa o le metadinlaadota (1,247). “E mu iyefun ti o kunna daradara, ki e si fi se buredi mejila, idamarun-un iwon iyefun efa kan ni ki e fi se buredi kookan. Nigba ti won de odo awon eniyan, okunrin kan wa sodo Jesu, o kunle niwaju re. Ero mi lori oro yii ni pe ohun ti o dara julo fun yin ni. Nigba ti ki i tii se pe e ti n se e nikan ni, sugbon tifetife ni e ti fi n se e lati odun ti o koja, Nitori ko si ohun ti o soro fun Olorun.” Laisi igi, ina oo ku,bee ni, laisi olofoofo, ija oo tan.E kiyesi awon ohun ti n sele si yin. Emi OLUWA awon omo ogun ni mo so bee. It is an insatiable Sango priest who names his son Bamigbose one should procure for oneself a ritual rod one can carry.
Avoid avarice. Oṣé is the ritual rod Ṣàngó priests carry; it is reputed to have the power to invoke lightning. The name Bámgbóṣé means “Help me carry a ritual rod.”
Avoid avarice. Ose is the ritual rod Sango priests carry; it is reputed to have the power to invoke lightning. The name Bamgbose means “Help me carry a ritual rod.”
kí ó lọ sọ fún Ebedimeleki ará Etiopia pé, OLUWA àwọn ọmọ ogun, Ọlọrun Israẹli ní, “Wò ó, n óo mú ìpinnu ibi tí mo ṣe lórí ìlú yìí ṣẹ, lójú rẹ ni yóo sì ṣẹ. Nítorí pé ìyè ni wọ́n jẹ́ fún àwọn tí ó rí wọn,ati ìwòsàn fún gbogbo ẹran ara wọn.ní Enrimoni, ní Sora, ati ní Jarimutu, Ọlọ́gbọ́n bẹẹrẹ-ẹ́ pète ìgárá.
ki o lo so fun Ebedimeleki ara Etiopia pe, OLUWA awon omo ogun, Olorun Israeli ni, “Wo o, n oo mu ipinnu ibi ti mo se lori ilu yii se, loju re ni yoo si se. Nitori pe iye ni won je fun awon ti o ri won,ati iwosan fun gbogbo eran ara won.ni Enrimoni, ni Sora, ati ni Jarimutu, Ologbon beere-e pete igara.
Láti inú oyún ni àwọn eniyan burúkú ti ṣìnà,láti ọjọ́ tí a ti bí wọn ni wọ́n tí ń ṣìṣe,tí wọn ń purọ́.Má jẹ́ kí ó ni ọ́ lára láti dá a sílẹ̀ kí ó sì máa lọ lọ́fẹ̀ẹ́, nítorí pé, ìdajì owó ọ̀yà alágbàṣe ni ó ti fi ń sìn ọ́, fún odidi ọdún mẹfa. Bẹ́ẹ̀ ni kí ẹ ṣe, kí OLUWA Ọlọrun yín lè bukun ohun gbogbo tí ẹ bá ń ṣe. Jehoiakini bọ́ aṣọ ẹ̀wọ̀n kúrò lọ́rùn, ó sì ń bá ọba jẹun lórí tabili ní gbogbo ọjọ́ ayé rẹ̀. O ti sọ wá di ẹni ẹ̀gàn lọ́wọ́ àwọn aládùúgbò wa;a di ẹni ẹ̀sín ati ẹni yẹ̀yẹ́ lọ́dọ̀ àwọn tí ó yí wa ká.Ẹni tí ń ṣiṣẹ́ oko dáradára, yóo ní oúnjẹ pupọ,ṣugbọn ẹni tí ń fi àkókò rẹ̀ ṣòfò yóo di talaka.àwọn ọmọ Barikosi, àwọn ọmọ Sisera, ati àwọn ọmọ Tema, ṣugbọn ó bi Farao ati àwọn ọmọ ogunrẹ̀ ṣubú ninu Òkun Pupa,nítorí pé ìfẹ́ rẹ̀ tí kì í yẹ̀ wà títí lae. Ọwọ́ mi óo tẹ̀ wọ́n; n óo sọ ilẹ̀ wọn di ahoro ati òkítì àlàpà, ní gbogbo ibùgbé wọn, láti ibi aṣálẹ̀ títí dé Ribila. Wọn óo wá mọ̀ nígbà náà pé èmi ni OLUWA.”Kí ni ó kàn wọ́n pẹlu ilé wọn mọ́, lẹ́yìn tí wọn bá ti kú,nígbà tí a bá ti ké ọjọ́ wọn kúrò lórí ilẹ̀.Nígbà tí ó parí àkókò tí yóo fi ṣiṣẹ́ alufaa ninu Tẹmpili, ó pada lọ sí ilé rẹ̀. Ó sọ fún wọn pé, “OLUWA Ọlọrun Israẹli ní, ‘Mo kó yín jáde wá láti Ijipti, mo gbà yín kalẹ̀ lọ́wọ́ àwọn ará Ijipti, ati gbogbo àwọn eniyan yòókù tí wọn ń ni yín lára.’ N óo gbẹ̀san ẹ̀jẹ̀ àwọn tí ẹ pa, n kò sì ní dá ẹlẹ́bi sí,nítorí èmi OLUWA ni mò ń gbé Sioni.”Ṣugbọn ẹ lọ, ẹ sọ fún àwọn ọmọ-ẹ̀yìn rẹ̀ ati Peteru pé ó ti lọ ṣáájú yín sí Galili, níbẹ̀ ni ẹ óo gbé rí i, gẹ́gẹ́ bí ó ti sọ fun yín.” sì gbọdọ bá A wá orogún. Òun
Lati inu oyun ni awon eniyan buruku ti sina,lati ojo ti a ti bi won ni won ti n sise,ti won n puro.Ma je ki o ni o lara lati da a sile ki o si maa lo lofee, nitori pe, idaji owo oya alagbase ni o ti fi n sin o, fun odidi odun mefa. Bee ni ki e se, ki OLUWA Olorun yin le bukun ohun gbogbo ti e ba n se. Jehoiakini bo aso ewon kuro lorun, o si n ba oba jeun lori tabili ni gbogbo ojo aye re. O ti so wa di eni egan lowo awon aladuugbo wa;a di eni esin ati eni yeye lodo awon ti o yi wa ka.Eni ti n sise oko daradara, yoo ni ounje pupo,sugbon eni ti n fi akoko re sofo yoo di talaka.awon omo Barikosi, awon omo Sisera, ati awon omo Tema, sugbon o bi Farao ati awon omo ogunre subu ninu Okun Pupa,nitori pe ife re ti ki i ye wa titi lae. Owo mi oo te won; n oo so ile won di ahoro ati okiti alapa, ni gbogbo ibugbe won, lati ibi asale titi de Ribila. Won oo wa mo nigba naa pe emi ni OLUWA.”Ki ni o kan won pelu ile won mo, leyin ti won ba ti ku,nigba ti a ba ti ke ojo won kuro lori ile.Nigba ti o pari akoko ti yoo fi sise alufaa ninu Tempili, o pada lo si ile re. O so fun won pe, “OLUWA Olorun Israeli ni, ‘Mo ko yin jade wa lati Ijipti, mo gba yin kale lowo awon ara Ijipti, ati gbogbo awon eniyan yooku ti won n ni yin lara.’ N oo gbesan eje awon ti e pa, n ko si ni da elebi si,nitori emi OLUWA ni mo n gbe Sioni.”Sugbon e lo, e so fun awon omo-eyin re ati Peteru pe o ti lo saaju yin si Galili, nibe ni e oo gbe ri i, gege bi o ti so fun yin.” si gbodo ba A wa orogun. Oun
lẹ̀mi n ké pẹ̀, ọdọ Rẹ̀ sì ni ìpadàsí
lemi n ke pe, odo Re si ni ipadasi
38.. Báyìí ni a sọ Ọ kalẹ̀ gẹgẹ bí
38.. Bayii ni a so O kale gege bi
ìdájọ tú hàn kedere.. Tí ìwọ bá
idajo tu han kedere.. Ti iwo ba
wá tẹ̀lé ìfẹkùfẹ tiwọn lẹhìn tí ìmọ
wa tele ifekufe tiwon lehin ti imo
ti dé wá bá ọ, kò ní sí
ti de wa ba o, ko ni si
Olùrànlọwọ tàbí aláààbò kankan
Oluranlowo tabi alaaabo kankan
fún ọ lọdọ Allah.
fun o lodo Allah.
ÌDÁ 6
IDA 6
39. Nítòôòtò. Àwa ti rán àwọn
39. Nitoooto. Awa ti ran awon
òjíṣẹ ṣíwájú rẹ̀. Àwa sì fún wọn
ojise siwaju re. Awa si fun won
ní àwọn ìyàwòú: àti àwọn ọmọ.
ni awon iyawou: ati awon omo.
Kò sì jẹ ohun tí ô ṣe € ṣe fún
Ko si je ohun ti o se € se fun
òjíṣ$ kan láti mú Àmì kan wá
ojis$ kan lati mu Ami kan wa
àyàfi nípa àṣẹ Allah. Ìgbà kòẹkan
ayafi nipa ase Allah. Igba koekan