NaijaRC / yor /dev.csv
Davlan's picture
Upload 8 files
72bf102 verified
raw
history blame
32.6 kB
year,story_id,story,question,options_A,options_B,options_C,options_D,Answer
2015,25,"Lẹ́yìn ogún ọdún tí Àbẹ̀ní ti wọlé ọkọ ni ó tó rọ́mọ bi. Ó ti relé aláwo, relé oníṣègùn fún ọ̀pọ̀lọpọ̀ ọdún. Gbogbo Ààfáà tí ó gbúròó agbára wọn ni ó ti dán wò pátá. Kódà, àìmọye oṣù ni ó ti lọ lábẹ́ àbò oríṣiríṣi wòlíì. Síbẹ̀ pàbó ni gbogbo rẹ̀ já sí. Ó ti sọ ìrètí nù pátápátá.
Gbogbo ayé ni ó ti rò ó pin. Àwẹ̀ní ìyá ọkọ rẹ̀ gbàgbọ́ pé ọkùnrin kì í yàgàn. Èyí ni ó mú un fẹ́ ìyàwó mìíràn fún ọmọ rẹ̀. Ọdún kejì tí Ìyábọ̀ wọlé Ọlálérè ni ó bí Adétọ́lá, ó sì tún bí Gbọ́láhàn àti Dàmọ́lá ní tẹ̀lé-ǹ-tẹ̀lé.
Nítorí pé ilẹ̀ àánú Ọlọ́run kì í ṣú, lẹ́yìn ogún ọdún tí Àbẹ̀ní ti wọlé ọkọ. Ọlọ́run dá a lóhùn. Ọlẹ̀ ayọ̀ sọ nínú un rẹ̀. Ìbẹta ni ó sì fi oyún náà bí.
","""Gbogbo aye ló ti rò ó pin"". Ta ni ""ó"" tọ́ka sí ninú àyọkà yìí?",Adétọ́lá,Àbẹ̀ní,Àwẹ̀ní,Ìyábọ̀,B
2015,25,"Lẹ́yìn ogún ọdún tí Àbẹ̀ní ti wọlé ọkọ ni ó tó rọ́mọ bi. Ó ti relé aláwo, relé oníṣègùn fún ọ̀pọ̀lọpọ̀ ọdún. Gbogbo Ààfáà tí ó gbúròó agbára wọn ni ó ti dán wò pátá. Kódà, àìmọye oṣù ni ó ti lọ lábẹ́ àbò oríṣiríṣi wòlíì. Síbẹ̀ pàbó ni gbogbo rẹ̀ já sí. Ó ti sọ ìrètí nù pátápátá.
Gbogbo ayé ni ó ti rò ó pin. Àwẹ̀ní ìyá ọkọ rẹ̀ gbàgbọ́ pé ọkùnrin kì í yàgàn. Èyí ni ó mú un fẹ́ ìyàwó mìíràn fún ọmọ rẹ̀. Ọdún kejì tí Ìyábọ̀ wọlé Ọlálérè ni ó bí Adétọ́lá, ó sì tún bí Gbọ́láhàn àti Dàmọ́lá ní tẹ̀lé-ǹ-tẹ̀lé.
Nítorí pé ilẹ̀ àánú Ọlọ́run kì í ṣú, lẹ́yìn ogún ọdún tí Àbẹ̀ní ti wọlé ọkọ. Ọlọ́run dá a lóhùn. Ọlẹ̀ ayọ̀ sọ nínú un rẹ̀. Ìbẹta ni ó sì fi oyún náà bí.
",Ta ni ó fẹ́ l̀yábọ̀ fún Ọlálérè?,Àwẹ̀ní,Àbẹ̀ní,Ààfáà,Wòlíì,A

",[MASK] ni àbígbẹ̀yìn l̀yábọ̀.,Gbọ́láhàn,l̀bẹta,Dàmọ́lá,Adétọ́lá,C
2015,25,"Lẹ́yìn ogún ọdún tí Àbẹ̀ní ti wọlé ọkọ ni ó tó rọ́mọ bi. Ó ti relé aláwo, relé oníṣègùn fún ọ̀pọ̀lọpọ̀ ọdún. Gbogbo Ààfáà tí ó gbúròó agbára wọn ni ó ti dán wò pátá. Kódà, àìmọye oṣù ni ó ti lọ lábẹ́ àbò oríṣiríṣi wòlíì. Síbẹ̀ pàbó ni gbogbo rẹ̀ já sí. Ó ti sọ ìrètí nù pátápátá.
Gbogbo ayé ni ó ti rò ó pin. Àwẹ̀ní ìyá ọkọ rẹ̀ gbàgbọ́ pé ọkùnrin kì í yàgàn. Èyí ni ó mú un fẹ́ ìyàwó mìíràn fún ọmọ rẹ̀. Ọdún kejì tí Ìyábọ̀ wọlé Ọlálérè ni ó bí Adétọ́lá, ó sì tún bí Gbọ́láhàn àti Dàmọ́lá ní tẹ̀lé-ǹ-tẹ̀lé.
Nítorí pé ilẹ̀ àánú Ọlọ́run kì í ṣú, lẹ́yìn ogún ọdún tí Àbẹ̀ní ti wọlé ọkọ. Ọlọ́run dá a lóhùn. Ọlẹ̀ ayọ̀ sọ nínú un rẹ̀. Ìbẹta ni ó sì fi oyún náà bí.
",Ọlálérè ni [MASK],Ààfáà,Wòlíì,ỌmỌ Àwẹ̀ní,Ọ̀rẹ́ oníṣègùn,C

",Àkọ́lé tí ó bá àyọkà yìí mu jù ni,Ènìyàn ń wojú Ọlọ́run ń wo ọkàn,Ẹ̀dá kò láròpin,Ọkùnrin kìí yàgàn,Àbẹ̀ní ìyá ìbẹta,B
2016,26,"Ọdún kejìlá rè é tí Adébáre, Adéyanjú àti Adéoyè ti wà ní Tòróńtò, ìlú ọba. Gbogbo wọn ló ti lówó. Adébáre nìkan ni ó pinnu láti wá dá ilé-iṣẹ́ sílẹ̀ ní Ajélàńwá, ìlú rẹ̀, nítorí pé ilé làbọ̀ ìsinmi oko. Ó sì tún rò pé yóò fún àwọn ará ìlú rẹ̀ ní àǹfààní láti ríṣẹ́ àti òwò ṣe.
Ní ọjọ́ ìṣílé-iṣẹ́ yìí, ìlú kún fọ́nfọ́n, ayé gbọ́ ọ̀rún sì mọ̀. Màlúù méjì ni ọba Àkànní, Alájé ti Ajélàńwá rà kalẹ̀ nítorí ìdùnnú tí ó ṣubú layọ̀ fún un pé àsìkò òun ni ilé-iṣẹ́ wọ̀lú. Ó dúpẹ́ lọ́wọ́ Adébáre fún àìgbàgbé ilé. Ó sì ṣí ilé-iṣẹ́ náà nípa gígé aṣọ tẹ́ẹ́rẹ́ tí a ta sí ẹnu ọ̀nà.
Nínú ilé-iṣẹ́ yìí ni a ti rí oríṣiríṣi ẹ̀ka bíi aṣọ híhun, ike ṣíṣe, búrẹ́dì ṣíṣe, abọ́ ìjẹun ṣíṣe àti ṣíṣe omi amọ́lóló. Àdépìtàn tí ó jẹ́ ọ̀gá ọlọ́pàá ní agbègbè yìí ṣèlérí ìpèse ààbò tó péye fún ilé-iṣẹ́ náà.",Adébáre nìkan ni ó,rántí ilé,rí tajé ṣe,pa màlúù,lọ sílùú ọba,A
2016,26,"Ọdún kejìlá rè é tí Adébáre, Adéyanjú àti Adéoyè ti wà ní Tòróńtò, ìlú ọba. Gbogbo wọn ló ti lówó. Adébáre nìkan ni ó pinnu láti wá dá ilé-iṣẹ́ sílẹ̀ ní Ajélàńwá, ìlú rẹ̀, nítorí pé ilé làbọ̀ ìsinmi oko. Ó sì tún rò pé yóò fún àwọn ará ìlú rẹ̀ ní àǹfààní láti ríṣẹ́ àti òwò ṣe.
Ní ọjọ́ ìṣílé-iṣẹ́ yìí, ìlú kún fọ́nfọ́n, ayé gbọ́ ọ̀rún sì mọ̀. Màlúù méjì ni ọba Àkànní, Alájé ti Ajélàńwá rà kalẹ̀ nítorí ìdùnnú tí ó ṣubú layọ̀ fún un pé àsìkò òun ni ilé-iṣẹ́ wọ̀lú. Ó dúpẹ́ lọ́wọ́ Adébáre fún àìgbàgbé ilé. Ó sì ṣí ilé-iṣẹ́ náà nípa gígé aṣọ tẹ́ẹ́rẹ́ tí a ta sí ẹnu ọ̀nà.
Nínú ilé-iṣẹ́ yìí ni a ti rí oríṣiríṣi ẹ̀ka bíi aṣọ híhun, ike ṣíṣe, búrẹ́dì ṣíṣe, abọ́ ìjẹun ṣíṣe àti ṣíṣe omi amọ́lóló. Àdépìtàn tí ó jẹ́ ọ̀gá ọlọ́pàá ní agbègbè yìí ṣèlérí ìpèse ààbò tó péye fún ilé-iṣẹ́ náà.",Ẹ̀ka mélòó ni ó wà nílé-iṣẹ́ náà?,Méjì,Mẹ́ta,Mẹ́rin,Márùn-ún,D
2016,26,"Ọdún kejìlá rè é tí Adébáre, Adéyanjú àti Adéoyè ti wà ní Tòróńtò, ìlú ọba. Gbogbo wọn ló ti lówó. Adébáre nìkan ni ó pinnu láti wá dá ilé-iṣẹ́ sílẹ̀ ní Ajélàńwá, ìlú rẹ̀, nítorí pé ilé làbọ̀ ìsinmi oko. Ó sì tún rò pé yóò fún àwọn ará ìlú rẹ̀ ní àǹfààní láti ríṣẹ́ àti òwò ṣe.
Ní ọjọ́ ìṣílé-iṣẹ́ yìí, ìlú kún fọ́nfọ́n, ayé gbọ́ ọ̀rún sì mọ̀. Màlúù méjì ni ọba Àkànní, Alájé ti Ajélàńwá rà kalẹ̀ nítorí ìdùnnú tí ó ṣubú layọ̀ fún un pé àsìkò òun ni ilé-iṣẹ́ wọ̀lú. Ó dúpẹ́ lọ́wọ́ Adébáre fún àìgbàgbé ilé. Ó sì ṣí ilé-iṣẹ́ náà nípa gígé aṣọ tẹ́ẹ́rẹ́ tí a ta sí ẹnu ọ̀nà.
Nínú ilé-iṣẹ́ yìí ni a ti rí oríṣiríṣi ẹ̀ka bíi aṣọ híhun, ike ṣíṣe, búrẹ́dì ṣíṣe, abọ́ ìjẹun ṣíṣe àti ṣíṣe omi amọ́lóló. Àdépìtàn tí ó jẹ́ ọ̀gá ọlọ́pàá ní agbègbè yìí ṣèlérí ìpèse ààbò tó péye fún ilé-iṣẹ́ náà.",Adépìtàn ni ó,fa màlúù kalẹ̀,dá ilé-iṣẹ́ sílẹ̀,gbàgbé ilé,ṣèlérí aàbò,D
2016,26,"Ọdún kejìlá rè é tí Adébáre, Adéyanjú àti Adéoyè ti wà ní Tòróńtò, ìlú ọba. Gbogbo wọn ló ti lówó. Adébáre nìkan ni ó pinnu láti wá dá ilé-iṣẹ́ sílẹ̀ ní Ajélàńwá, ìlú rẹ̀, nítorí pé ilé làbọ̀ ìsinmi oko. Ó sì tún rò pé yóò fún àwọn ará ìlú rẹ̀ ní àǹfààní láti ríṣẹ́ àti òwò ṣe.
Ní ọjọ́ ìṣílé-iṣẹ́ yìí, ìlú kún fọ́nfọ́n, ayé gbọ́ ọ̀rún sì mọ̀. Màlúù méjì ni ọba Àkànní, Alájé ti Ajélàńwá rà kalẹ̀ nítorí ìdùnnú tí ó ṣubú layọ̀ fún un pé àsìkò òun ni ilé-iṣẹ́ wọ̀lú. Ó dúpẹ́ lọ́wọ́ Adébáre fún àìgbàgbé ilé. Ó sì ṣí ilé-iṣẹ́ náà nípa gígé aṣọ tẹ́ẹ́rẹ́ tí a ta sí ẹnu ọ̀nà.
Nínú ilé-iṣẹ́ yìí ni a ti rí oríṣiríṣi ẹ̀ka bíi aṣọ híhun, ike ṣíṣe, búrẹ́dì ṣíṣe, abọ́ ìjẹun ṣíṣe àti ṣíṣe omi amọ́lóló. Àdépìtàn tí ó jẹ́ ọ̀gá ọlọ́pàá ní agbègbè yìí ṣèlérí ìpèse ààbò tó péye fún ilé-iṣẹ́ náà.",Kín ni àǹfààní tí ó ṣe pàtàkì jù lára ìṣílé-iṣẹ́ yìí?,Rírí aṣọ ìgbàlódé wọ̀,Pípọ̀ oúnjẹ nílùú,Rírí omi tí ó dára mu,Pípèsè iṣẹ́ àti ọ̀nà òwò,D
2016,26,"Ọdún kejìlá rè é tí Adébáre, Adéyanjú àti Adéoyè ti wà ní Tòróńtò, ìlú ọba. Gbogbo wọn ló ti lówó. Adébáre nìkan ni ó pinnu láti wá dá ilé-iṣẹ́ sílẹ̀ ní Ajélàńwá, ìlú rẹ̀, nítorí pé ilé làbọ̀ ìsinmi oko. Ó sì tún rò pé yóò fún àwọn ará ìlú rẹ̀ ní àǹfààní láti ríṣẹ́ àti òwò ṣe.
Ní ọjọ́ ìṣílé-iṣẹ́ yìí, ìlú kún fọ́nfọ́n, ayé gbọ́ ọ̀rún sì mọ̀. Màlúù méjì ni ọba Àkànní, Alájé ti Ajélàńwá rà kalẹ̀ nítorí ìdùnnú tí ó ṣubú layọ̀ fún un pé àsìkò òun ni ilé-iṣẹ́ wọ̀lú. Ó dúpẹ́ lọ́wọ́ Adébáre fún àìgbàgbé ilé. Ó sì ṣí ilé-iṣẹ́ náà nípa gígé aṣọ tẹ́ẹ́rẹ́ tí a ta sí ẹnu ọ̀nà.
Nínú ilé-iṣẹ́ yìí ni a ti rí oríṣiríṣi ẹ̀ka bíi aṣọ híhun, ike ṣíṣe, búrẹ́dì ṣíṣe, abọ́ ìjẹun ṣíṣe àti ṣíṣe omi amọ́lóló. Àdépìtàn tí ó jẹ́ ọ̀gá ọlọ́pàá ní agbègbè yìí ṣèlérí ìpèse ààbò tó péye fún ilé-iṣẹ́ náà.",Àkọ́lé tí ó bá àyọkà yìí mu jùlọ ni,l̀Iú Tòróńtò,Ilé làbọ̀ ìsinmi oko,ilé- iṣẹ́ Adébáre,Ayẹyẹ ìṣílé-iṣẹ́,B
2016,27,"Ọmọ bíbí ìlú Béyìíòṣe ni Ìṣọ̀lá. Òun àti àbúrò rẹ̀ Fọláhànmí, nìkan ni Bádéjọ, bàbá wọ́n bí. Àgbẹ̀ oníkòkó aládàáńlá ni Bádéjọ. Bọ́látitó, aya rẹ̀ sì jẹ́ oníṣòwò obì. Bádéjọ kò kàwé ṣùgbọ́n ó pinnu láti tọ́ àwọn ọmọ rẹ̀ méjéèjì débi tí wọ́n bá lè kàwé dé láyé, nítorí pé ìya àìkàwé jẹ ẹ́ púpọ̀ nídi òwò tí ó ń ṣe.
Lẹ́yìn tí Ìṣọ̀lá parí ìwé mẹ́wàá ní ìlú l̀bòdì ni ó gba ìlú Arómisá lọ láti tẹ̀ síwáiú nínú ẹ̀kọ́ rẹ̀ ní fásitì. Ìlú ọbá ni ó sì ti gba oyè ìmọ̀ ìjìnlẹ̀ kejì nínú òfin. Ìṣọ̀lá padà sílúu Béyìíròṣe, ó sì di gbajúgbajà agbẹjọ́rò káàkiri agbègbè náà.",Ilú abínibí Bádéjọ ni,Ìbòdì,Arómisá,Béyìíòṣe,Ìlú-ọba,C
2016,27,"Ọmọ bíbí ìlú Béyìíòṣe ni Ìṣọ̀lá. Òun àti àbúrò rẹ̀ Fọláhànmí, nìkan ni Bádéjọ, bàbá wọ́n bí. Àgbẹ̀ oníkòkó aládàáńlá ni Bádéjọ. Bọ́látitó, aya rẹ̀ sì jẹ́ oníṣòwò obì. Bádéjọ kò kàwé ṣùgbọ́n ó pinnu láti tọ́ àwọn ọmọ rẹ̀ méjéèjì débi tí wọ́n bá lè kàwé dé láyé, nítorí pé ìya àìkàwé jẹ ẹ́ púpọ̀ nídi òwò tí ó ń ṣe.
Lẹ́yìn tí Ìṣọ̀lá parí ìwé mẹ́wàá ní ìlú l̀bòdì ni ó gba ìlú Arómisá lọ láti tẹ̀ síwáiú nínú ẹ̀kọ́ rẹ̀ ní fásitì. Ìlú ọbá ni ó sì ti gba oyè ìmọ̀ ìjìnlẹ̀ kejì nínú òfin. Ìṣọ̀lá padà sílúu Béyìíròṣe, ó sì di gbajúgbajà agbẹjọ́rò káàkiri agbègbè náà.",Bádéjọ pinnu láti tọ́ àwọn ọmọ rẹ̀ ní ẹ̀kọ́-ìwé nítorí pé,ó ní owó,kò bímọ púpọ̀,ó fẹ́ di bàbá alákọ̀wé,l̀ya àìkàwé jẹ ẹ́,D
2016,27,"Ọmọ bíbí ìlú Béyìíòṣe ni Ìṣọ̀lá. Òun àti àbúrò rẹ̀ Fọláhànmí, nìkan ni Bádéjọ, bàbá wọ́n bí. Àgbẹ̀ oníkòkó aládàáńlá ni Bádéjọ. Bọ́látitó, aya rẹ̀ sì jẹ́ oníṣòwò obì. Bádéjọ kò kàwé ṣùgbọ́n ó pinnu láti tọ́ àwọn ọmọ rẹ̀ méjéèjì débi tí wọ́n bá lè kàwé dé láyé, nítorí pé ìya àìkàwé jẹ ẹ́ púpọ̀ nídi òwò tí ó ń ṣe.
Lẹ́yìn tí Ìṣọ̀lá parí ìwé mẹ́wàá ní ìlú l̀bòdì ni ó gba ìlú Arómisá lọ láti tẹ̀ síwáiú nínú ẹ̀kọ́ rẹ̀ ní fásitì. Ìlú ọbá ni ó sì ti gba oyè ìmọ̀ ìjìnlẹ̀ kejì nínú òfin. Ìṣọ̀lá padà sílúu Béyìíròṣe, ó sì di gbajúgbajà agbẹjọ́rò káàkiri agbègbè náà.",Ìbòdì ni,a bí Ìṣọ̀lá sí,Ìṣọ̀lá ti gboyè ẹlẹ́ẹ̀kejì,Ìṣọ̀lá tí kàwé mẹ́wàá,Ìṣọ̀lá ti ń ṣiṣẹ́ agbẹjọ́rò,C
2016,27,"Ọmọ bíbí ìlú Béyìíòṣe ni Ìṣọ̀lá. Òun àti àbúrò rẹ̀ Fọláhànmí, nìkan ni Bádéjọ, bàbá wọ́n bí. Àgbẹ̀ oníkòkó aládàáńlá ni Bádéjọ. Bọ́látitó, aya rẹ̀ sì jẹ́ oníṣòwò obì. Bádéjọ kò kàwé ṣùgbọ́n ó pinnu láti tọ́ àwọn ọmọ rẹ̀ méjéèjì débi tí wọ́n bá lè kàwé dé láyé, nítorí pé ìya àìkàwé jẹ ẹ́ púpọ̀ nídi òwò tí ó ń ṣe.
Lẹ́yìn tí Ìṣọ̀lá parí ìwé mẹ́wàá ní ìlú l̀bòdì ni ó gba ìlú Arómisá lọ láti tẹ̀ síwáiú nínú ẹ̀kọ́ rẹ̀ ní fásitì. Ìlú ọbá ni ó sì ti gba oyè ìmọ̀ ìjìnlẹ̀ kejì nínú òfin. Ìṣọ̀lá padà sílúu Béyìíròṣe, ó sì di gbajúgbajà agbẹjọ́rò káàkiri agbègbè náà.",Fọláhànmí jẹ́,àbúro Ìṣọ̀lá,ẹ̀gbọ́n Ìṣọ̀lá,Oníṣòwò obì,àgbẹ̀ oníkòkó,A
2016,27,"Ọmọ bíbí ìlú Béyìíòṣe ni Ìṣọ̀lá. Òun àti àbúrò rẹ̀ Fọláhànmí, nìkan ni Bádéjọ, bàbá wọ́n bí. Àgbẹ̀ oníkòkó aládàáńlá ni Bádéjọ. Bọ́látitó, aya rẹ̀ sì jẹ́ oníṣòwò obì. Bádéjọ kò kàwé ṣùgbọ́n ó pinnu láti tọ́ àwọn ọmọ rẹ̀ méjéèjì débi tí wọ́n bá lè kàwé dé láyé, nítorí pé ìya àìkàwé jẹ ẹ́ púpọ̀ nídi òwò tí ó ń ṣe.
Lẹ́yìn tí Ìṣọ̀lá parí ìwé mẹ́wàá ní ìlú l̀bòdì ni ó gba ìlú Arómisá lọ láti tẹ̀ síwáiú nínú ẹ̀kọ́ rẹ̀ ní fásitì. Ìlú ọbá ni ó sì ti gba oyè ìmọ̀ ìjìnlẹ̀ kejì nínú òfin. Ìṣọ̀lá padà sílúu Béyìíròṣe, ó sì di gbajúgbajà agbẹjọ́rò káàkiri agbègbè náà.",Àkọ́lé tí ó bá àyọkà yìí mu jùlọ ni,Ààbọ̀ ẹ̀kọ́,Ọmọ bẹẹrẹ,Àǹfààní ẹ̀kọ́ ìwé,iṣẹ́ àgbẹ̀ àǹfààní,C
2017,28,"""Ẹ firun dúdú ṣiṣẹ́."" Gbólóhún yìí ni bàbá àgbà, Adélabí, máa ń fi ṣí àwọn ọmọọmọ rẹ̀ létí ní gbogbo ìgbà. Ìgbà tí wọ́n bá wá kí ibúlé Ológo ló máa ń ráyè ṣe èyí. Àyọ̀ká àti Gbénró kọ́kọ́ máa ń kọtí ọ̀gbọn-in sí àwọn ọ̀rọ ìṣítí wọ̀nyí ṣùgbọ́n nígbà tí wọ́n ríi pé àwọn ẹ̀gbọ́n wọn, Ọlá àti Bíọ́dún, tó ń tẹ̀lé ìmọ̀ràn yìí ń mókè nínú ẹ̀kọ́ wọn, ni àwọn náà bá yára fara mọ́ ọ. Síbẹ̀síbẹ̀, Ọláníkẹ̀ẹ́ ní tirẹ̀ kò já gbogbo rẹ̀ kúnra.
Nítorí ìdí èyí, kò wá yani lẹ́nu pé nígbà tí wọ́n dàgbà tán, gbogbo àwọn tó tẹ̀lé ọ̀rọ ìṣítí bàbá àgbà ló mókè: wọ́n di akọ́ṣẹ́mọṣẹ́ ní ẹ̀ka iṣẹ́ tí wọ́n yàn Iáàyò; wọ́n wá là, tí wọ́n sì lu. Ọláníkẹ̀ẹ́ ni tirẹ̀ wá gúnlẹ̀ sí Ọjàaba níbi tó ti ń gbàárù.","Nínú àwọn tí bàbá àgbá sọ̀rọ̀ ìṣítí fún, mélòó ló mókè?",Ọ̀kan,Méjì,Mẹ́ta,Mẹ́rin,D
2017,28,"""Ẹ firun dúdú ṣiṣẹ́."" Gbólóhún yìí ni bàbá àgbà, Adélabí, máa ń fi ṣí àwọn ọmọọmọ rẹ̀ létí ní gbogbo ìgbà. Ìgbà tí wọ́n bá wá kí ibúlé Ológo ló máa ń ráyè ṣe èyí. Àyọ̀ká àti Gbénró kọ́kọ́ máa ń kọtí ọ̀gbọn-in sí àwọn ọ̀rọ ìṣítí wọ̀nyí ṣùgbọ́n nígbà tí wọ́n ríi pé àwọn ẹ̀gbọ́n wọn, Ọlá àti Bíọ́dún, tó ń tẹ̀lé ìmọ̀ràn yìí ń mókè nínú ẹ̀kọ́ wọn, ni àwọn náà bá yára fara mọ́ ọ. Síbẹ̀síbẹ̀, Ọláníkẹ̀ẹ́ ní tirẹ̀ kò já gbogbo rẹ̀ kúnra.
Nítorí ìdí èyí, kò wá yani lẹ́nu pé nígbà tí wọ́n dàgbà tán, gbogbo àwọn tó tẹ̀lé ọ̀rọ ìṣítí bàbá àgbà ló mókè: wọ́n di akọ́ṣẹ́mọṣẹ́ ní ẹ̀ka iṣẹ́ tí wọ́n yàn Iáàyò; wọ́n wá là, tí wọ́n sì lu. Ọláníkẹ̀ẹ́ ni tirẹ̀ wá gúnlẹ̀ sí Ọjàaba níbi tó ti ń gbàárù.",Ohun tí ó mú kí Àyọ̀ká àti Gbénró yi ìwà padà ni,mímókè àwọn ẹ̀gbọ́n wọn,Ìbẹ̀rù àti di alágbàárù,lílọ sí abúlé Ológo,ọ̀rọ bàbá àgbà,A
2017,28,"""Ẹ firun dúdú ṣiṣẹ́."" Gbólóhún yìí ni bàbá àgbà, Adélabí, máa ń fi ṣí àwọn ọmọọmọ rẹ̀ létí ní gbogbo ìgbà. Ìgbà tí wọ́n bá wá kí ibúlé Ológo ló máa ń ráyè ṣe èyí. Àyọ̀ká àti Gbénró kọ́kọ́ máa ń kọtí ọ̀gbọn-in sí àwọn ọ̀rọ ìṣítí wọ̀nyí ṣùgbọ́n nígbà tí wọ́n ríi pé àwọn ẹ̀gbọ́n wọn, Ọlá àti Bíọ́dún, tó ń tẹ̀lé ìmọ̀ràn yìí ń mókè nínú ẹ̀kọ́ wọn, ni àwọn náà bá yára fara mọ́ ọ. Síbẹ̀síbẹ̀, Ọláníkẹ̀ẹ́ ní tirẹ̀ kò já gbogbo rẹ̀ kúnra.
Nítorí ìdí èyí, kò wá yani lẹ́nu pé nígbà tí wọ́n dàgbà tán, gbogbo àwọn tó tẹ̀lé ọ̀rọ ìṣítí bàbá àgbà ló mókè: wọ́n di akọ́ṣẹ́mọṣẹ́ ní ẹ̀ka iṣẹ́ tí wọ́n yàn Iáàyò; wọ́n wá là, tí wọ́n sì lu. Ọláníkẹ̀ẹ́ ni tirẹ̀ wá gúnlẹ̀ sí Ọjàaba níbi tó ti ń gbàárù.",Ìgbà wo ni bàbá àgbà máa ń ráyè fún àwọn ọmọọmọ rẹ̀ ní ìṣítí?,Nígbà tí wọ́n bá mókè nínú ẹ̀kọ́ wọn,Nígbà tí wọ́n ń kẹ́kọ̀ọ́,Nígbà tí wọ́n bá wa kí i lábúlé,Nígbà tí wọ́n di akọ́ṣẹ́mọṣẹ́,C
2017,28,"""Ẹ firun dúdú ṣiṣẹ́."" Gbólóhún yìí ni bàbá àgbà, Adélabí, máa ń fi ṣí àwọn ọmọọmọ rẹ̀ létí ní gbogbo ìgbà. Ìgbà tí wọ́n bá wá kí ibúlé Ológo ló máa ń ráyè ṣe èyí. Àyọ̀ká àti Gbénró kọ́kọ́ máa ń kọtí ọ̀gbọn-in sí àwọn ọ̀rọ ìṣítí wọ̀nyí ṣùgbọ́n nígbà tí wọ́n ríi pé àwọn ẹ̀gbọ́n wọn, Ọlá àti Bíọ́dún, tó ń tẹ̀lé ìmọ̀ràn yìí ń mókè nínú ẹ̀kọ́ wọn, ni àwọn náà bá yára fara mọ́ ọ. Síbẹ̀síbẹ̀, Ọláníkẹ̀ẹ́ ní tirẹ̀ kò já gbogbo rẹ̀ kúnra.
Nítorí ìdí èyí, kò wá yani lẹ́nu pé nígbà tí wọ́n dàgbà tán, gbogbo àwọn tó tẹ̀lé ọ̀rọ ìṣítí bàbá àgbà ló mókè: wọ́n di akọ́ṣẹ́mọṣẹ́ ní ẹ̀ka iṣẹ́ tí wọ́n yàn Iáàyò; wọ́n wá là, tí wọ́n sì lu. Ọláníkẹ̀ẹ́ ni tirẹ̀ wá gúnlẹ̀ sí Ọjàaba níbi tó ti ń gbàárù.",Ta ni ó sọ pé ẹnu àgbà ń rùn?,Àyọ̀ká,Gbénró,Ọláníkẹ̀ẹ́,Bíọ́dún,C
2017,28,"""Ẹ firun dúdú ṣiṣẹ́."" Gbólóhún yìí ni bàbá àgbà, Adélabí, máa ń fi ṣí àwọn ọmọọmọ rẹ̀ létí ní gbogbo ìgbà. Ìgbà tí wọ́n bá wá kí ibúlé Ológo ló máa ń ráyè ṣe èyí. Àyọ̀ká àti Gbénró kọ́kọ́ máa ń kọtí ọ̀gbọn-in sí àwọn ọ̀rọ ìṣítí wọ̀nyí ṣùgbọ́n nígbà tí wọ́n ríi pé àwọn ẹ̀gbọ́n wọn, Ọlá àti Bíọ́dún, tó ń tẹ̀lé ìmọ̀ràn yìí ń mókè nínú ẹ̀kọ́ wọn, ni àwọn náà bá yára fara mọ́ ọ. Síbẹ̀síbẹ̀, Ọláníkẹ̀ẹ́ ní tirẹ̀ kò já gbogbo rẹ̀ kúnra.
Nítorí ìdí èyí, kò wá yani lẹ́nu pé nígbà tí wọ́n dàgbà tán, gbogbo àwọn tó tẹ̀lé ọ̀rọ ìṣítí bàbá àgbà ló mókè: wọ́n di akọ́ṣẹ́mọṣẹ́ ní ẹ̀ka iṣẹ́ tí wọ́n yàn Iáàyò; wọ́n wá là, tí wọ́n sì lu. Ọláníkẹ̀ẹ́ ni tirẹ̀ wá gúnlẹ̀ sí Ọjàaba níbi tó ti ń gbàárù.",Àkọ́lé tí ó bá àyọkà yìí mu jù ni,Àwọn akọ́ṣẹ́mọṣẹ́,Ìgbọ́ràn dára,Àìmàsìkò ló ń dàmú ẹ̀dá,Aláàárù Ọjàaba,B
2017,29,"Ìbòòsí o, ẹ máa jẹ́ kí àṣà ó wòòkùn. Àṣà Yorùbá ò mà gbọdọ̀ parun-un. Mo wo ṣàkun ọ̀rọ̀, mo rí i pé ọ̀pọ̀ àkóónú àṣa Yorùbá làṣa àtọ̀húnrìnwá ti fẹ́ẹ́ tì sí kòtò.
Bọ́ládé oníkẹ̀kẹ́ bímọ tán nídalẹ̀, ó fi àáké kọ́ri pé wọn ò gbọdọ̀ kọmọ òun nílà ojú. Ó ṣe àtọ́kasí pe Jìnádù bí tiẹ̀ ní Èkó, kò kọlà fún un: Làmídì bí tiẹ̀ ní Kútúweeji kò sín in ní gbẹ́rẹ́ débi ilà. Ó tún fàáké kọ́rí pé kò sí ohun tí ń jẹ́ ẹsẹ̀-n-táyé; ó ní àbámọdá ni. Oríkì ìdílé, ọfọ̀ ni, kò ní ìtumọ̀ kankan sí òun, ó ti gbàgbé Àlàbá àti Jèémìsì, ọ̀rẹ́ rẹ̀, tí wọ́n kọ ilà ojú fún ọmọ tiwọn.
Àṣẹ̀yìnwá àṣẹ̀yìnbọ̀, wọ́n lé wọn nílùú tí wọ́n ń gbé. Wọ́n padà dèrò ìlú abínibí wọn. Wọ́n dà wọ́n sílẹ̀ bíi iyanrìn tí típà kó; wọ́n ní kí kálùkù gbalé bàbá rẹ̀ lọ. Bọ́ládé sì ti kú nígbà tí à ń wí yìí; àwọn ọmọ rẹ̀ kò mọlé mọ́, wọn kò mọ ìran wọn débi tí wọn ó mọ oríkì. Wọ́n dàrè nílée bàba wọn. Jídé ọmọ Jìnádù di oníṣẹ́ méjì, múrí kan. Ó ń bá oníṣẹ́ ṣiṣẹ́ nítorí pé kò béèrè ìtẹsẹwáyé rẹ̀. Ẹni tó sọ ilé nù, ó so àpò ìyà kọ́!",Ki ni ó fa sábàbí àṣà Yorùbá tó fẹ́ẹ́ wòòkùn?,Ìbòòsí,Àṣa àjèèjì,Àpẹ́jù ní ìdálẹ̀,Iṣẹ́,B
2017,29,"Ìbòòsí o, ẹ máa jẹ́ kí àṣà ó wòòkùn. Àṣà Yorùbá ò mà gbọdọ̀ parun-un. Mo wo ṣàkun ọ̀rọ̀, mo rí i pé ọ̀pọ̀ àkóónú àṣa Yorùbá làṣa àtọ̀húnrìnwá ti fẹ́ẹ́ tì sí kòtò.
Bọ́ládé oníkẹ̀kẹ́ bímọ tán nídalẹ̀, ó fi àáké kọ́ri pé wọn ò gbọdọ̀ kọmọ òun nílà ojú. Ó ṣe àtọ́kasí pe Jìnádù bí tiẹ̀ ní Èkó, kò kọlà fún un: Làmídì bí tiẹ̀ ní Kútúweeji kò sín in ní gbẹ́rẹ́ débi ilà. Ó tún fàáké kọ́rí pé kò sí ohun tí ń jẹ́ ẹsẹ̀-n-táyé; ó ní àbámọdá ni. Oríkì ìdílé, ọfọ̀ ni, kò ní ìtumọ̀ kankan sí òun, ó ti gbàgbé Àlàbá àti Jèémìsì, ọ̀rẹ́ rẹ̀, tí wọ́n kọ ilà ojú fún ọmọ tiwọn.
Àṣẹ̀yìnwá àṣẹ̀yìnbọ̀, wọ́n lé wọn nílùú tí wọ́n ń gbé. Wọ́n padà dèrò ìlú abínibí wọn. Wọ́n dà wọ́n sílẹ̀ bíi iyanrìn tí típà kó; wọ́n ní kí kálùkù gbalé bàbá rẹ̀ lọ. Bọ́ládé sì ti kú nígbà tí à ń wí yìí; àwọn ọmọ rẹ̀ kò mọlé mọ́, wọn kò mọ ìran wọn débi tí wọn ó mọ oríkì. Wọ́n dàrè nílée bàba wọn. Jídé ọmọ Jìnádù di oníṣẹ́ méjì, múrí kan. Ó ń bá oníṣẹ́ ṣiṣẹ́ nítorí pé kò béèrè ìtẹsẹwáyé rẹ̀. Ẹni tó sọ ilé nù, ó so àpò ìyà kọ́!",Ta ni kò gbà kí wọ́n kọlà fún ọmọ òun?,Àlàbá,Bóládé,Jèémíìsì,Jídé,B
2017,29,"Ìbòòsí o, ẹ máa jẹ́ kí àṣà ó wòòkùn. Àṣà Yorùbá ò mà gbọdọ̀ parun-un. Mo wo ṣàkun ọ̀rọ̀, mo rí i pé ọ̀pọ̀ àkóónú àṣa Yorùbá làṣa àtọ̀húnrìnwá ti fẹ́ẹ́ tì sí kòtò.
Bọ́ládé oníkẹ̀kẹ́ bímọ tán nídalẹ̀, ó fi àáké kọ́ri pé wọn ò gbọdọ̀ kọmọ òun nílà ojú. Ó ṣe àtọ́kasí pe Jìnádù bí tiẹ̀ ní Èkó, kò kọlà fún un: Làmídì bí tiẹ̀ ní Kútúweeji kò sín in ní gbẹ́rẹ́ débi ilà. Ó tún fàáké kọ́rí pé kò sí ohun tí ń jẹ́ ẹsẹ̀-n-táyé; ó ní àbámọdá ni. Oríkì ìdílé, ọfọ̀ ni, kò ní ìtumọ̀ kankan sí òun, ó ti gbàgbé Àlàbá àti Jèémìsì, ọ̀rẹ́ rẹ̀, tí wọ́n kọ ilà ojú fún ọmọ tiwọn.
Àṣẹ̀yìnwá àṣẹ̀yìnbọ̀, wọ́n lé wọn nílùú tí wọ́n ń gbé. Wọ́n padà dèrò ìlú abínibí wọn. Wọ́n dà wọ́n sílẹ̀ bíi iyanrìn tí típà kó; wọ́n ní kí kálùkù gbalé bàbá rẹ̀ lọ. Bọ́ládé sì ti kú nígbà tí à ń wí yìí; àwọn ọmọ rẹ̀ kò mọlé mọ́, wọn kò mọ ìran wọn débi tí wọn ó mọ oríkì. Wọ́n dàrè nílée bàba wọn. Jídé ọmọ Jìnádù di oníṣẹ́ méjì, múrí kan. Ó ń bá oníṣẹ́ ṣiṣẹ́ nítorí pé kò béèrè ìtẹsẹwáyé rẹ̀. Ẹni tó sọ ilé nù, ó so àpò ìyà kọ́!","Nínú àyọkà yìí, kí ni ẹnìkán pè ní àbámọdá?",Ọfọ̀,llà kíkọ,Oríkì,Ẹsẹ̀-n-táyé,D
2017,29,"Ìbòòsí o, ẹ máa jẹ́ kí àṣà ó wòòkùn. Àṣà Yorùbá ò mà gbọdọ̀ parun-un. Mo wo ṣàkun ọ̀rọ̀, mo rí i pé ọ̀pọ̀ àkóónú àṣa Yorùbá làṣa àtọ̀húnrìnwá ti fẹ́ẹ́ tì sí kòtò.
Bọ́ládé oníkẹ̀kẹ́ bímọ tán nídalẹ̀, ó fi àáké kọ́ri pé wọn ò gbọdọ̀ kọmọ òun nílà ojú. Ó ṣe àtọ́kasí pe Jìnádù bí tiẹ̀ ní Èkó, kò kọlà fún un: Làmídì bí tiẹ̀ ní Kútúweeji kò sín in ní gbẹ́rẹ́ débi ilà. Ó tún fàáké kọ́rí pé kò sí ohun tí ń jẹ́ ẹsẹ̀-n-táyé; ó ní àbámọdá ni. Oríkì ìdílé, ọfọ̀ ni, kò ní ìtumọ̀ kankan sí òun, ó ti gbàgbé Àlàbá àti Jèémìsì, ọ̀rẹ́ rẹ̀, tí wọ́n kọ ilà ojú fún ọmọ tiwọn.
Àṣẹ̀yìnwá àṣẹ̀yìnbọ̀, wọ́n lé wọn nílùú tí wọ́n ń gbé. Wọ́n padà dèrò ìlú abínibí wọn. Wọ́n dà wọ́n sílẹ̀ bíi iyanrìn tí típà kó; wọ́n ní kí kálùkù gbalé bàbá rẹ̀ lọ. Bọ́ládé sì ti kú nígbà tí à ń wí yìí; àwọn ọmọ rẹ̀ kò mọlé mọ́, wọn kò mọ ìran wọn débi tí wọn ó mọ oríkì. Wọ́n dàrè nílée bàba wọn. Jídé ọmọ Jìnádù di oníṣẹ́ méjì, múrí kan. Ó ń bá oníṣẹ́ ṣiṣẹ́ nítorí pé kò béèrè ìtẹsẹwáyé rẹ̀. Ẹni tó sọ ilé nù, ó so àpò ìyà kọ́!","Ta ni ""oníṣẹ́ méjì, múrí kan""?",Jídé,Bọ́ládé,Jìnádù,Làmídì,A
2017,29,"Ìbòòsí o, ẹ máa jẹ́ kí àṣà ó wòòkùn. Àṣà Yorùbá ò mà gbọdọ̀ parun-un. Mo wo ṣàkun ọ̀rọ̀, mo rí i pé ọ̀pọ̀ àkóónú àṣa Yorùbá làṣa àtọ̀húnrìnwá ti fẹ́ẹ́ tì sí kòtò.
Bọ́ládé oníkẹ̀kẹ́ bímọ tán nídalẹ̀, ó fi àáké kọ́ri pé wọn ò gbọdọ̀ kọmọ òun nílà ojú. Ó ṣe àtọ́kasí pe Jìnádù bí tiẹ̀ ní Èkó, kò kọlà fún un: Làmídì bí tiẹ̀ ní Kútúweeji kò sín in ní gbẹ́rẹ́ débi ilà. Ó tún fàáké kọ́rí pé kò sí ohun tí ń jẹ́ ẹsẹ̀-n-táyé; ó ní àbámọdá ni. Oríkì ìdílé, ọfọ̀ ni, kò ní ìtumọ̀ kankan sí òun, ó ti gbàgbé Àlàbá àti Jèémìsì, ọ̀rẹ́ rẹ̀, tí wọ́n kọ ilà ojú fún ọmọ tiwọn.
Àṣẹ̀yìnwá àṣẹ̀yìnbọ̀, wọ́n lé wọn nílùú tí wọ́n ń gbé. Wọ́n padà dèrò ìlú abínibí wọn. Wọ́n dà wọ́n sílẹ̀ bíi iyanrìn tí típà kó; wọ́n ní kí kálùkù gbalé bàbá rẹ̀ lọ. Bọ́ládé sì ti kú nígbà tí à ń wí yìí; àwọn ọmọ rẹ̀ kò mọlé mọ́, wọn kò mọ ìran wọn débi tí wọn ó mọ oríkì. Wọ́n dàrè nílée bàba wọn. Jídé ọmọ Jìnádù di oníṣẹ́ méjì, múrí kan. Ó ń bá oníṣẹ́ ṣiṣẹ́ nítorí pé kò béèrè ìtẹsẹwáyé rẹ̀. Ẹni tó sọ ilé nù, ó so àpò ìyà kọ́!",Àkọ́lé tí ó bá àyọkà yìí mu jù ni,Àṣà àjèjì ti dọba,llé làbọ̀ ìsinmi oko,Bọ́ládé àti ẹbí rẹ̀,Àṣà abínibí ò gbọdọ̀ kú.,D