news_title
stringlengths
23
128
label
class label
7 classes
date
stringlengths
15
18
bbc_url_id
stringlengths
8
8
Coronavirus: Nàìjíríà sọ àgádágodo sí ilé ìtajà China l‘Abuja láti dènà ìtànkálẹ̀ Coronavirus
2health
30 Oṣù Ṣẹ́rẹ́ 2020
51306436
Oluwo: Oluwo fárígá pẹ̀lú ìjọba àpapọ̀ lórí àgbékalẹ̀ iléèwé ẹ̀kọ́ṣẹ́ olùkọ́ni
3nigeria
7 Oṣù Ṣẹ́rẹ́ 2020
51016799
AFCON 2019: Àmì ayò tí Nàíjíríà àti South Afrika gbá rèé
5sport
10 Oṣù Agẹmọ 2019
48940362
Ajimobi: Orúkọ èmi, Akala, Ladoja, Adebayo Faleti àtàwọn míì
4politics
15 Oṣù Ẹ̀bibi 2019
48278572
Deji Adeyanju: Àwọn olólùfẹ́ Ààrẹ Buhari kọlu Deji Adeyanju àtàwọn ajàfẹ́tọ̀ọ́ tó wọ́de l'Abuja
4politics
23 Oṣù Ọ̀pẹ̀ 2019
50896221
Tí mo bá rí obìnrin tó kò níṣẹ́ lápá, mó máa ń ní kí wọ́n wò mí ṣe àríkọ́gbọ́n
3nigeria
8 Oṣù Èrèlè 2020
51424983
YCE: Ìpínlẹ kọ̀ọ̀kan ní àṣẹ láti dá ààbò bo àwọ̀n ènìyàn wọn
3nigeria
15 Oṣù Ṣẹ́rẹ́ 2020
51106499
Davido: Àpètàn orukọ̀ ọmọ tuntun náà ní David Adedeji Ifeanyi Adeleke
1entertainment
20 Oṣù Ọ̀wàrà 2019
50114244
Daddy Freeze: 'Kátàkárà ni owó orí gbígbà lórí ọmọbìnrin jẹ́'
1entertainment
31 Oṣù Ògún 2019
49533852
Libya Refugees: Àtìpó 162 míì dé padà láti Libya
0africa
30 Oṣù Ṣẹ́rẹ́ 2019
47053059
Mínísítà 43 ni Ààrẹ Muhammadu Buhari ṣe ìbúra fún to yàn sípò
4politics
21 Oṣù Ògún 2019
49420415
ASSU Strike: Ìpàdé ASUU àti ìjọba tún forí sánpọ́n
3nigeria
18 Oṣù Ọ̀pẹ̀ 2018
46600055
Yollywood: Odunlade fijó bẹ́ẹ, Lizzy padà sọ́dún 2012, Lateef gbàmì ẹ̀yẹ tuntun
1entertainment
12 Oṣù Ọ̀wàrà 2019
50025256
Sanwo-Olu: Àtàrí Àjànàkú ni àkóso Eko, kì í ṣe ẹrù ọmọdé
4politics
7 Oṣù Òkúdu 2019
48563650
Seyi Makinde: Gbogbo iṣẹ́ àgbàṣe tí Ajimọbi ṣe lẹ́yìn ìbò ní màá gbéyẹ̀wò
4politics
25 Oṣù Ẹrẹ̀nà 2019
47689998
Ondo police: Ìwádìí ń tẹ̀síwájú lórí ìjínigbé náà
3nigeria
8 Oṣù Bélú 2018
46135670
Nigeria Elections 2019: Dapo Abiodun, ǹkan márùn ún tó yẹ kẹ́ẹ mọ̀ nípa rẹ̀
4politics
26 Oṣù Ṣẹ́rẹ́ 2019
46509255
Afenifere: Ìgbà wo ni Bola Tinubu di ọmọ ẹgbẹ Afenifere?
4politics
26 Oṣù Òkúdu 2019
48770589
Oluwo: Ó dàbí ẹni pé ọ̀tá pọ̀ fún mi, inú wọn kò dùn sí bí mo ṣe ń ṣakọ
1entertainment
22 Oṣù Èrèlè 2020
51582952
Gani Adams: Kò bá dáa tí INEC bá sùn ọjọ́ gbígba PVC síwájú
4politics
7 Oṣù Èrèlè 2019
47161640
Mọ̀ síi nípa Yakubu tó wọ bàtà tí Jẹ́gà bọ́ sílẹ̀ ni INEC
4politics
22 Oṣù Ṣẹ́rẹ́ 2019
46563336
Adewale Ayuba: Ogun ń ja àgbo Fújì, ni wọ́n ṣe ń jà
1entertainment
7 Oṣù Òkúdu 2019
48556341
BOWEN: Àwọn adarí ti fásitì Bowen pa lẹ́yìn wàhálà àwọn akẹ́kọ̀ọ́
3nigeria
3 Oṣù Ọ̀pẹ̀ 2018
46424101
Lagos crime: Àáfà ní òun bu ọlọ́pàá jẹ nígbà tó fẹ́ yí òun lọ́rùn ní Mushin
3nigeria
2 Oṣù Bélú 2019
50275054
NLC: Gbogbo òṣiṣẹ ló n fẹ́ ilọsiwaju Naijiria
3nigeria
23 Oṣù Ọ̀pẹ̀ 2018
46664079
ICPC vs Kashamu: Irọ́ ni ICPC ń pa mọ́ Kashamu lórí ọ̀rọ̀ ọkọ̀ áńbúlàǹsì àti ẹ̀rọ amúnáwá
3nigeria
27 Oṣù Owewe 2019
49848910
Tinubu 2023': 'Èmi kọ́ lò rán ẹgbẹ́ 'Asiwaju Reloaded Ambassadors' níṣẹ́ o'
4politics
10 Oṣù Agẹmọ 2019
48934293
Lassa fever: Ìjọba Eko ní akẹ́kọ̀ọ́ fásitì Ebonyi tó wá kẹ́kọ́ ìmọ̀ òfin, ní wọ́n bá Lassa lára rẹ̀
2health
20 Oṣù Èrèlè 2020
51569246
Lagos Building Collapse: Ìjọba ìpínlẹ̀ Eko gbé ìgbìmọ̀ olùwádìí kalẹ̀
3nigeria
21 Oṣù Ẹrẹ̀nà 2019
47649973
Man Utd Vs Man City: Kò ṣèlẹ́rí! àwọn alatilẹyin Liverpool yóò gbè lẹyìn Man Utd
5sport
25 Oṣù Ìgbé 2019
48040825
Akure Anglican Bursar: Àwọn agbébọn gbé owó sálọ lẹ́yìn tí wọ́n pa akápò ìjọ Anglican
3nigeria
5 Oṣù Ìgbé 2019
47817422
NNPC: Ìwádìí ti bẹ̀rẹ̀ lórí ohun tó fa ìjàmbá iná ọ̀pá epo tó wáyé l'Abule Egba
3nigeria
20 Oṣù Ọ̀pẹ̀ 2018
46629631
Herbal Medicine: Gbígboyè fásítì nínú iṣẹ́ ìṣègùn ìbílẹ̀ dára, àrídájú gbọdọ̀ wà lórí rẹ̀
2health
31 Oṣù Ògún 2019
49533853
Ìdílé kan gbé ilé iṣẹ́ ọkọ̀ òfurufú lọ ilé ẹjọ́ lẹ́yìn tí wọ́n léwọ̀n dànù nínú ọkọ̀ pé ara wọ́n ń rùn
6world
31 Oṣù Ṣẹ́rẹ́ 2020
51333304
Kogi Election: Dino Melaye náà pariwo pé àwọn apanìyàn ti gbòde ní ìbò ku ọ̀la
4politics
15 Oṣù Bélú 2019
50430963
Osun Politics: Aregbesola ní irọ́ n'ìròyìn tó ń sọ pé aáwọ̀ wà láàrín òun àti gómìnà Oyetola
4politics
21 Oṣù Ọ̀pẹ̀ 2019
50877009
Atiku: Màá foríji àwọn tó bá dá owó ìlú tí wọ́n kó jẹ padà
4politics
31 Oṣù Ṣẹ́rẹ́ 2019
47053762
Yewande Oyediran: Kò sí ohun tó burú nínú bí Ajimobi ṣe dá Yewande tó pa ọkọ rẹ̀ sílẹ̀
3nigeria
22 Oṣù Agẹmọ 2019
49069273
Ẹ̀ wo àwòrán ìgbé ayé Robert Mugabe!
0africa
6 Oṣù Owewe 2019
49604433
Illegal Orphanage: Ìjọba ti ayédèrú ilé ọmọ aláìlóbìí pa, ọmọdé mẹ́tàdínlọ́gbọ̀n gbòmìnira
3nigeria
9 Oṣù Ṣẹ́rẹ́ 2020
51044318
NLC Strike: Mínísítà fọ́rọ̀ òṣíṣẹ́ pe ìpàdé àwọn olórí òṣìṣẹ́ lọ́jọ́ Ìṣẹ́gun
3nigeria
14 Oṣù Ọ̀wàrà 2019
50038637
Ìgbìmọ̀ iṣedajọ orílè-èdè Nàìjíríà NJC nikan lo le yọ adajọ-Amofin
3nigeria
3 Oṣù Ìgbé 2019
47800769
DR Congo: Àwùjọ àgbáyé ń polongo àláàfíà nítorí èsì ìdìbò ààrẹ
0africa
11 Oṣù Ṣẹ́rẹ́ 2019
46820240
Chioma Ikeaza-Uzodinma tí wọ́n ṣẹ̀ṣẹ̀ búra wọlé fún ọkọ rẹ̀ ní Imo
4politics
16 Oṣù Ṣẹ́rẹ́ 2020
51136999
Sex for Grades: Fásitì Eko ní kí olùkọ́ míì lọ fìdímọ́lé lori Fídíò BBC
3nigeria
9 Oṣù Ọ̀wàrà 2019
49989843
Lagos State: Ìjọba ìpínlẹ̀ Eko ní irọ́ ni àjọ EIU ń pa pé ìlú Eko ló léwu jùlọ láti gbé lágbàáyé
3nigeria
2 Oṣù Owewe 2019
49547939
Ààrẹ Donald Trump: Qasem Soleimani ń gbìmọ̀ràn láti kọ lù wá l'Amerika la ṣe kọ́kọ́ yára pa á - Trump Ààrẹ
6world
4 Oṣù Ṣẹ́rẹ́ 2020
50991770
Kogi àti Bayelsa: Gomina Yahaya Bello ti Kogi àti David Lyon ti Bayelsa gba ìwé ẹ̀rí INEC
4politics
21 Oṣù Bélú 2019
50507329
Toyin Abraham: Àwọn ohun tó yẹ ko mọ̀ nípa Toyin Abraham
1entertainment
5 Oṣù Owewe 2019
49590233
Omolola Ajayi: Gloria Bright ní ọ̀gá òun kọ̀ láti sanwó oṣù fún òun lẹ́yìn oṣù mẹ́ta
1entertainment
15 Oṣù Ṣẹ́rẹ́ 2020
51113621
Female Driver: Sokunbi ni obìnrin àwakọ̀ Dáńfó l‘Eko, tó ń lọ̀ láti ìpínlẹ̀ kan sí òmíì
3nigeria
20 Oṣù Èrèlè 2020
51569477
Amotekun: Ìjọba Eko kéde pé òun ní ẹ̀ṣọ́ aláàbò tẹ́lẹ̀, òun kò sí ní yí orúkọ rẹ̀ padá sí Amotekun
3nigeria
14 Oṣù Èrèlè 2020
51499506
Irú kí leyi,iná jó òkú méjìlá mọ inú ílé ìgbókúpamọ́sí OAU
3nigeria
19 Oṣù Bélú 2019
50476508
Ibadan High Chiefs: Àwọn Olóyè Ibadan mọ́kànlélógún tó ń pe ara wọn lọ́ba ń fi ẹ̀wọ̀n run imú
1entertainment
31 Oṣù Ọ̀pẹ̀ 2019
50953801
Prophecy 2020: Primate Ayodele, Baba Adeboye àti Father Mbaka sọ àsọtẹ́lẹ̀ nípa 2020!
3nigeria
12 Oṣù Ṣẹ́rẹ́ 2020
50966248
University of Transportation Daura: Nǹkan mẹ́wàá tó yẹ ní mímọ̀ nípa fásitì ẹ̀kọ́ ìrìnnà
3nigeria
3 Oṣù Ọ̀pẹ̀ 2019
50633480
Amẹrika dá akẹ́kọ́ọ̀ Harvard pada sí orílẹ̀-èdè rẹ̀ nítori ǹkan ọ̀rẹ́ rẹ̀ kọ lóri ayálujára
6world
28 Oṣù Ògún 2019
49499934
Ooni: Mo rọ àwọn àgbẹ̀ àti darandaran láti gba ìrẹ́pọ̀ láàyè
3nigeria
5 Oṣù Ògún 2019
49232191
Kaduna Kidnapping - Ọmọ iléèwé mẹfà pẹlú Olùkọ méjì ni wọn jígbé ni Kaduna.
3nigeria
3 Oṣù Ọ̀wàrà 2019
49923538
Akitoshi Okamoto: Òṣìṣẹ́fẹ̀yìntì, wọ gbaga ọlọ́pàá torí pé o pé ní 24,000
3nigeria
4 Oṣù Ọ̀pẹ̀ 2019
50649565
Yollywood: Àwọn èèyàn fèsì pé Kemi ń díbọ́n ni, tórí ọ̀rọ̀ ọkùnrin ni
1entertainment
16 Oṣù Ọ̀wàrà 2019
50070206
PDP: A ò fẹ́ ẹ̀jẹ̀ Buhari gẹ́gẹ́ bí alábojútó ìbò kíkà
4politics
3 Oṣù Ṣẹ́rẹ́ 2019
46750564
#Zamfarakillings: Ìjọba pàṣẹ kí wọn dáwọ́ ìwakùsà ní Zamfara
3nigeria
8 Oṣù Ìgbé 2019
47846150
R Kelly: Èmi kò jẹ̀bi ẹ̀ṣùn fífi ipá bá ọmọdé lòpọ̀
1entertainment
7 Oṣù Ẹrẹ̀nà 2019
47482067
America: Ẹ má dúró ju ìṣẹ́jú mẹ́wàá lọ níta ìlú yóò tutù kọjá àlà
6world
30 Oṣù Ṣẹ́rẹ́ 2019
47053058
Lizzy Anjorin: Ẹ má bú mi, ọ̀pọ̀ òṣèré tíátà ni kìí bá mi yọ̀ fún ire mi
1entertainment
24 Oṣù Ògún 2019
49457496
Ìtàn Mánigbàgbé: £100, tíí ṣe ₦42,150 àsìkò yìí, nìjọba fun Taiwo Akinkunmi lówó iṣẹ́ lọ́dún 1959
1entertainment
28 Oṣù Òkúdu 2019
48786545
Kí gan an ni ẹgbẹ́ NURTW ní ṣe pẹ̀lú òṣèlú Nàìjíríà?
4politics
12 Oṣù Ṣẹ́rẹ́ 2019
46834336
El-Zakzaky pé ìpàdé pẹ̀lú àwọn àgbẹ́joro India àti àwọn àjọ ti kìí ṣe ti ìjọba
3nigeria
16 Oṣù Ògún 2019
49367174
Marriage Certificate: Bí o ṣe lè mọ ìgbéyàwó tí kò bá òfin mu
1entertainment
27 Oṣù Agẹmọ 2019
49137279
Aláàfin ìlú Oyo ti bímọ okùnrin tuntun lẹ́ni odún 81
1entertainment
17 Oṣù Èrèlè 2020
51528235
N11trn subsidy: Ǹjẹ́ ẹ mọ̀ pé owó ìrànwọ́ epo lè kọ Second Niger Bridge méjìléláàdọ́ta?
3nigeria
31 Oṣù Ẹ̀bibi 2019
48470559
Burger: Kunle Afod, Sindodo, Lola Alao se ìdárò ẹni to lọ
1entertainment
4 Oṣù Ṣẹ́rẹ́ 2019
46756129
Àjọ Fifa fòfin de Samson Siasia títí láíláí
5sport
16 Oṣù Ògún 2019
49375316
Lórí ọ̀rọ̀ Pásítọ̀ COZA àti Dakolo, Ìwadìí ń tẹ̀ síwájú, ṣùgbọ́n a kò mọ ohunkohun nípa rẹ̀ mọ́- Iléeṣẹ́ ọlọ́pàá Èkó
1entertainment
22 Oṣù Agẹmọ 2019
49068226
Sasa Market: Seriki Hausa ní ogún èèyàn ló farapa nínú ìjà Ṣasa
3nigeria
2 Oṣù Ògún 2019
49211442
Àwọn agbófinró ń wá ọlọ́pàá tó yìnbọn lu olólùfẹ̀ẹ́ méjì, lẹ́yìn tí wọ́n gbé akẹgbẹ́ẹ̀ rẹ̀
3nigeria
14 Oṣù Ìgbé 2019
47925386
Lagos Fire Service: Ẹ máse tan àbẹ́là lórí ike tàbí pákó
3nigeria
24 Oṣù Ṣẹ́rẹ́ 2019
46943676
Birth tourism: Ẹ̀yin obìnrin tẹ́ẹ fẹ́ wá bímọ ní America, ọ̀nà ti tì pa látònì! - Trump
6world
24 Oṣù Ṣẹ́rẹ́ 2020
51232655
INEC: Àwọn ẹgbẹ́ òṣèlú yóò dìbò àbẹ́lé lóṣù Kẹjọ
4politics
10 Oṣù Ìgbé 2019
47866945
Kunle Afod: Ohun mẹ́wàá tó yẹ́ kí o mọ̀ nípa Kunle Afod ti Yollywood
1entertainment
24 Oṣù Ọ̀wàrà 2019
50165784
Olùkọ kan àti àwọn mẹ́ẹ̀dógún míràn ni wọn ti yẹgi fún ní Bangladesh
6world
25 Oṣù Ọ̀wàrà 2019
50178919
9th Assembly: Èrò ṣe ọ̀tọ̀ọ̀tọ̀ lórí ẹní tí àṣẹ ilé aṣòfin àgbà Nàìjíríà yóò já mọ́ lọ́wọ́
4politics
11 Oṣù Òkúdu 2019
48588672
Adio Atawẹwẹ: Orin Fuji ló gba iwé kíkà lọ́wọ́ mi
1entertainment
24 Oṣù Agẹmọ 2019
49100660
Sebótimọ Ẹlẹ́wà Sàpọ́n - Ó ń rọ̀ wá láti má se kọjá agbára wa
1entertainment
3 Oṣù Ọ̀pẹ̀ 2018
46423374
Carabao cup: Iheanacho gba góòlù wọlé láti ra Leicester city padà lọ́wọ́ ìfìdírẹmi
5sport
9 Oṣù Ṣẹ́rẹ́ 2020
51044377
Supreme court judgement: Ta ni Gómìnà Bala Mohammed?
3nigeria
21 Oṣù Ṣẹ́rẹ́ 2020
51188959
Ilé Aṣòfin Eko: A fẹ́ mọ̀ bí Ambode ṣé nà ₦45b tó fi ra BRT
3nigeria
28 Oṣù Ògún 2019
49492926
Kogi àti Bayelsa: Èsì ìbò tó jáde láti ìpínlẹ̀ Kogi
4politics
18 Oṣù Bélú 2019
50449797
ECOWAS: Buhari nàka àbùkù s'orílẹ̀èdè Libya látàrí aàbò tó mẹ́hẹ l'Afrika
0africa
22 Oṣù Ọ̀pẹ̀ 2019
50883192
#BBCNigeria2019: Ààrẹ Buhari ní ìdìbò ọjọ́ Àbámẹ́ta yóò lọ n'ìrọwọ́ rọsẹ̀
4politics
15 Oṣù Èrèlè 2019
47246078
Gas Explosion: Ènìyàn márùn ún ti jáláìsí látàri ìjàmbá afẹfẹ gáàsì Kaduna
3nigeria
5 Oṣù Ṣẹ́rẹ́ 2020
50993732
Léyìn òpọ̀lọ̀pò ọdún àgbàọ̀jẹ̀ agbábọ́ọ̀lù ọmọ Cameroun ní òun ti dé wáàsimi
0africa
7 Oṣù Owewe 2019
49619060
Amole festival in Akure: Deji pàṣẹ kí gbogbo ọjà àti ṣọ́ọ̀bù wà ní títì pa
1entertainment
30 Oṣù Ògún 2019
49521080
Atiku vs Buhari: Adájọ́ yóò ṣẹ̀dájọ́ lóní lórí ìbò ààrẹ Naijiria
4politics
11 Oṣù Owewe 2019
49652864
Nigeria swearing-in 2019: Wo àwòrán tó jẹ ojú ní gbèsè nípa ìbúra ààrẹ àtàwọn gómìnà
4politics
29 Oṣù Ẹ̀bibi 2019
48449967
Aregbesola: Ó se bẹbẹ ní ọdún mẹ́jọ tó fi sèjọba l‘Ọ́sun
4politics
27 Oṣù Bélú 2018
46352795
Wo àwọn ọ̀gá ọlọ́pàá tuntun mẹ́tàlá tí àjọ ọ̀hún fọ́nka síta
3nigeria
9 Oṣù Bélú 2019
50358673
Organisation of Islamic Cooperation: Àǹfààní wo ló wà nínú ẹgbẹ́ OIC?
6world
30 Oṣù Ẹ̀bibi 2019
48457001
Shiite: Ilé ẹjọ́ gíga Kaduna sún ìgbẹ́jọ́ adarí Shiite síwájú
3nigeria
29 Oṣù Agẹmọ 2019
49153823