news_title
stringlengths
23
128
label
class label
7 classes
date
stringlengths
15
18
bbc_url_id
stringlengths
8
8
Abu Bakr al-Baghdad: Orílẹ̀èdè Amẹrika náà ti kọlu aṣaájú ẹgbẹ́ ISIS
6world
27 Oṣù Ọ̀wàrà 2019
50198266
Number Plate: Ìlànà FRSC rèé láti gba nọ́mbà àdáni fún ọkọ̀ rẹ
3nigeria
4 Oṣù Bélú 2019
50285589
Facebook yóò bẹ̀rẹ̀ ìnáwó orí ayélujára 'GlobalCoin' lọ́dún 2020
6world
24 Oṣù Ẹ̀bibi 2019
48396351
COZA: A ti wọ́gilé ìwọ́de lórí COZA tí a fẹ́ ṣe tẹ́lẹ́ nítorí...
1entertainment
17 Oṣù Agẹmọ 2019
49018321
Ẹ wo bí ìjíròrò ṣe lọ láàrin àwọn olùdíje gómìnà Kwara
4politics
11 Oṣù Ṣẹ́rẹ́ 2019
46821239
Soyinka: Ohun gbogbo ti dẹnu kọlẹ̀ la ṣe gbọdọ̀ gbé ìgbésẹ̀ pàjáwìrì
3nigeria
9 Oṣù Ògún 2019
49289063
Aguda Ogba Fire: Iná míì tún sọ ní Ọgba, nílùú Eko!
3nigeria
24 Oṣù Ṣẹ́rẹ́ 2020
51193900
Xenophobia: Ọrò ajé llè South Africa ti ń rẹ̀yìn lọ́wọ́lọ́wọ́
0africa
27 Oṣù Owewe 2019
49782600
Afeez Owo: Abiyamọ gidi ní Funmi martins, ìyá ìyàwó mi
1entertainment
5 Oṣù Bélú 2019
50306224
Ondo Police: À ń wá Deji Adenuga tó dáná sun ènìyàn mẹ́jọ
3nigeria
24 Oṣù Ìgbé 2019
48034264
APC: O jẹ́ tètè jẹ́wọ́ àwọn tó rán ọ níṣẹ́ torí àwa kìí fún apààyàn lówó
4politics
25 Oṣù Ògún 2019
49463848
CCT: Adájọ́ fẹ̀yìntì ní àwọn asòfin àpapọ̀ yẹ kó fòǹtẹ̀ lu ìgbẹ́jọ́ adájọ́ àgbà
3nigeria
14 Oṣù Ṣẹ́rẹ́ 2019
46860346
2019 elections: Awọn jàǹdùkú yìnbọn f'éèyàn méjì nítorí owó ní Kwara
4politics
7 Oṣù Ẹrẹ̀nà 2019
47487258
Ayinla Kollington: Ìyàwó mí títí láéláé ni Salawa Abẹni
1entertainment
19 Oṣù Agẹmọ 2019
49046364
Europa league: Ìjàmbà tún ṣe Ole àtàwọn ọmọ rẹ níwájú AZ Alkmaar, ọ̀mì ni wọ́n ta
5sport
3 Oṣù Ọ̀wàrà 2019
49924361
2019 Elections: Ìpàdé ìtagbangba BBC Yorùba ń ṣẹlẹ̀ ní gbọ̀ngàn fásitì ìlú Ilorin
4politics
10 Oṣù Ṣẹ́rẹ́ 2019
46744386
Ramadan: Àwọn mùsùlùmí tí kò bẹ̀rẹ̀ àwẹ̀ títí d'ìgbà tí wọ́n tó fojú r'óṣù
6world
8 Oṣù Ẹ̀bibi 2019
48192282
Xenophobia: Ọ̀sẹ̀ tó ń bọ̀ ni bàálù yóò lọ kó ọmọ Nàíjíríà wálé
0africa
7 Oṣù Owewe 2019
49618865
Èyí ni bí àwọn agbébọn ṣe gbé òṣìṣẹ́ Shell méjì, wọ́n tún pa àwọ̀n aláàbò wọ̀n ní Rivers
3nigeria
27 Oṣù Ìgbé 2019
48076058
Alaafin: Ẹ máa kọ́ àwọn ọmọ wa ní èdé àti àṣà Yorùbá
1entertainment
26 Oṣù Ògún 2019
49470429
Anambra mortuary: Ọ̀pọ̀lọpọ̀ òkú jóná di eérú nínú iná tó jó ní mọ́ṣúárì Anambra
3nigeria
30 Oṣù Ọ̀pẹ̀ 2018
46716813
Ìtàn Mánigbàgbé: Kí lo fẹ́ mọ̀ nípa ‘Ajala Travels’?
1entertainment
7 Oṣù Owewe 2019
46096298
Katsina: Ó di ìgbàkẹ́tà l'óṣù kan tí àṣírí ilé ìmúni nígbèkùn yóò tú síta ní àríwá Nàìjíríà
3nigeria
15 Oṣù Ọ̀wàrà 2019
50061220
Olufunke Oshonaike: Ewu ń bẹ fún àwọn obìnrin tó ń fẹ́ ọkọ ọlọ́kọ
1entertainment
26 Oṣù Owewe 2019
49835940
Ìpànìyàn: Agbébọn pa 16 ní Benue, jàǹdùkú 59 kú ní Zamfara
3nigeria
21 Oṣù Èrèlè 2019
47315017
Nigeria Swearing in 2019: Makinde ní omi tuntun rú, ìgbà ọ̀tun dé sí ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́
4politics
29 Oṣù Ẹ̀bibi 2019
48447062
Electoral bill 2018: Buhari àtàwọn aṣòfin àpapọ̀ leè gbéná wojú ara wọn láìpẹ́
4politics
6 Oṣù Ọ̀pẹ̀ 2018
46464330
Obasanjọ pàrọọwà sí Makinde: yàgò fún òṣèlú sọ ọ́ sápò
4politics
15 Oṣù Ẹrẹ̀nà 2019
47573525
Nigeria 2019 Elections: Tinubu ní òun yóò sàjọyọ̀ ìsẹ́gun lọ́sẹ̀ tó ń bọ̀
4politics
21 Oṣù Èrèlè 2019
47308007
Botswana: Ìdí tí erin àti òkúta Dáyámọ́ǹdì yóò fi leè sọ olúborí èsì ètò ìdìbò ààrẹ
0africa
22 Oṣù Ọ̀wàrà 2019
50143867
Oluwo, ó yẹ kí o bọ̀wọ̀ fún ara rẹ - Olorì àná, Chanel Chin
1entertainment
28 Oṣù Ọ̀pẹ̀ 2019
50934195
Ìṣẹ̀lẹ̀ ìpànìyàn: Iléeṣẹ́ aṣọ́bodè ní àṣìta ìbọn ló fa sábàbí
3nigeria
19 Oṣù Èrèlè 2019
47288658
JAMB Result 2019: 34,120 akẹ́ẹ̀kọ́ ni kò ní èsì ìdańwò JAMB
3nigeria
11 Oṣù Ẹ̀bibi 2019
48239453
Ondo Doctors‘ Strike: Ọ̀pọ̀ dókítà ni wọ́n jẹ́ lowó oṣù mẹ́ta sí mẹ́fà
2health
10 Oṣù Ṣẹ́rẹ́ 2020
51063830
Nollywood: Taiwo Hassan, akọni òṣèré Yollywood tó jẹ́.....
1entertainment
31 Oṣù Ọ̀wàrà 2019
50245381
BB Naija 2019: Ọlọ́pàá Gẹ̀ẹ́sì bẹ̀rẹ̀ ìwádìí lórí Khafi lórí ẹ̀sùn ṣíṣe ìbálòpọ̀
1entertainment
13 Oṣù Ògún 2019
49327963
End of a decade: Àwọn ìròyìn mẹ́wàá tó mí ilẹ̀ titi láàrin ọdún 2010-2019
1entertainment
30 Oṣù Ọ̀pẹ̀ 2019
50951882
Electoral bill 2018: Èrèèdí wàhálà láàárín Buhari àtàwọn aṣòfin àpapọ̀ lórí òfin ìdìbò 2018
4politics
6 Oṣù Ọ̀pẹ̀ 2018
46464333
Onitsha market fire: Ilé tó lé ni 100 ló bá ìṣẹ̀lẹ̀ ìjàmbá iná lọ ní Onitsha
3nigeria
17 Oṣù Ọ̀wàrà 2019
50078577
Election Tribunal: INEC ní òfin kò ní kí èsì ìbò ààrẹ wà lórí ''server''
4politics
14 Oṣù Òkúdu 2019
48637089