news_title
stringlengths
23
128
label
class label
7 classes
date
stringlengths
15
18
bbc_url_id
stringlengths
8
8
Fatai Owoseni: O dìgbà tí mo bá bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ kí ń tó sọ ìpinnu mi
3nigeria
19 Oṣù Ògún 2019
49392592
Dandan ni bàyíì fún àwọn màálù ni Uganda láti gba ìwé ọjọ́ ìbí
0africa
19 Oṣù Agẹmọ 2019
49042173
Àwọn ǹkan tí yóò t'ẹyin kíkógbá iléeṣẹ́ tó n sójú Nàìjíríà nílẹ̀ láwọn orílè-èdè márùn
3nigeria
22 Oṣù Ẹ̀bibi 2019
48363333
#NigeriaDecides: Àwọn ohun to ní láti mọ̀ ní pa idibò 2019
4politics
15 Oṣù Èrèlè 2019
47255615
Fasiti Ọbafẹmi Awolowo University, Ọọni ile ifẹ takorawọn lórí ẹ̀sùn májèlé táwọn kan dà sómi iléèwé náà
3nigeria
11 Oṣù Ìgbé 2019
47892693
8th National Assembly: Ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin kẹ̀jọ kógbá sílé lónìí
4politics
6 Oṣù Òkúdu 2019
48539474
Kano Supplementary Election: Àwọn ẹgbẹ́ òṣèlú 42 tàpá sí èsì ìbò àtúndì Kano
4politics
26 Oṣù Ẹrẹ̀nà 2019
47709492
UEFA Champions League 2019: ilé ló máa bọ́sí fàwọn ọmọ Afrika loni
5sport
1 Oṣù Òkúdu 2019
48483022
Miliọnu kan naira nileeṣẹ to ba fiya jẹ àkàndá ẹ̀dá a san lówó ìtanràn
2health
24 Oṣù Ṣẹ́rẹ́ 2019
46983539
Day 22: Njẹ́ ẹni tí yóó borí ní ìdìbò 2019 ṣe pàtàkì bí?
4politics
25 Oṣù Ṣẹ́rẹ́ 2019
46998199
Mike Zhang dì ọmọ China akọkọ tí wọ́n f'oye dá lọla ní ìpínlẹ̀ Kano
3nigeria
26 Oṣù Ìgbé 2019
48055533
Bobrisky sàlàyé ipò tó wà gẹ́gẹ́ bi ọkunrin tàbí obinrin
1entertainment
3 Oṣù Bélú 2019
50279411
Orílẹ̀-èdè Togo gbe òfin tuntun silẹ̀ lórí ìwọ́de ìfẹ̀hónu hàn
0africa
9 Oṣù Ògún 2019
49286924
#China_kills_Muslims: Àwọn èèyàn bọ́ sórí Twitter lórí ìfìyàjẹ musulumi lọ́wọ́ọ China
6world
22 Oṣù Ọ̀pẹ̀ 2019
50885962
Premiership league: Liverpool fẹ́rẹ̀ ẹ́ forígbá níwájú Southampton ṣùgbọ́n orí kó o yọ
5sport
17 Oṣù Ògún 2019
49382556
Ìgbà mélòó ní wọn fẹ kéde ikú ẹṣọ tó pá Ọ̀gágun Lorílè-èdè Ethiopia ?
0africa
25 Oṣù Òkúdu 2019
48754423
Lagos State: Ẹbí èèyàn márùn ún àti àlejò kú sínú ilé l'Eko
3nigeria
4 Oṣù Owewe 2019
49583651
El-Zakzaky: Ọ̀pọ̀ ẹ̀sùn aṣemáṣe ni ìjọba àpapọ̀ fi kan Zakzaky ní India
3nigeria
15 Oṣù Ògún 2019
49354867
Parties Deregulation: Olapade Agoro ní INEC kò fi tó àwọn léti pé ó fẹ́ wọ́gilé 74 ẹgbẹ́ òṣèlú
4politics
7 Oṣù Èrèlè 2020
51410589
Ekiti Sack: Kí ló dé tí àwọn ìjọba ń yọ òṣìṣẹ́ bíi ẹní yọ jìgá ní gbogbo ìgbà?
3nigeria
16 Oṣù Ẹ̀bibi 2019
48292748
Ìròyìn Kàyééfì BBC Yorùbá: Bí Ọba aládé ṣe jàjà bọ́ lọ́wọ́ àwọn afurasí ajínigbé
3nigeria
28 Oṣù Owewe 2019
49856848
Davido: Kí ló fa ariwo lórí ìdọ́rẹ́ òun àti Chioma aya rẹ̀ lójú òpó Instagram?
1entertainment
18 Oṣù Ṣẹ́rẹ́ 2020
51162338
Àwọn ọmọ Nàìjíríà kan fẹ́ kí ilé ẹjọ́ ó fagilé orúkọ Buhari gẹ́gẹ́ bi olùdíje APC
4politics
29 Oṣù Agẹmọ 2019
49149623
Mother Language Day: Ẹgbẹ́ Akọ́mọlédè l‘Eko ṣe káre sí BBC Yorùbá fún àgbéga àṣà
1entertainment
22 Oṣù Èrèlè 2020
51595690
UK: Fiona Onasanya parọ́ pé òun kọ́ ló wa ọkọ̀ sáré àsájù
6world
30 Oṣù Ṣẹ́rẹ́ 2019
47044904
Sugar: Iléẹjọ́ ní àwọn afurasí mẹ́rin kò mọwọ́-mẹsẹ̀ lórí ikú Sugar
1entertainment
23 Oṣù Ṣẹ́rẹ́ 2020
51225515
Police arrest: 'Ó léwu láti kọ́kọ́ yẹ ọlọ́pàá wò ní Nàìjíríà'
3nigeria
14 Oṣù Ẹ̀bibi 2019
48266890
China - Rògbòdìyàn bẹ sílẹ lọjọ òmìnira àádọ́rin ọdún ilẹ China
6world
1 Oṣù Ọ̀wàrà 2019
49892673
Ìtàn Mánigbàgbé: Hubert Ogunde jẹ́ kọ́sítébù ọlọ́pàá àti olùkọ́, kó to bẹ̀rẹ̀ eré síse
1entertainment
18 Oṣù Ọ̀pẹ̀ 2019
46251738
Presidential Debate:Atiku yọjú, ó kọ̀ láti kópa
4politics
19 Oṣù Ṣẹ́rẹ́ 2019
46932307
Àwọn olùgbé Maiduguri ìṣoro ni àpọ̀jù iná mọ̀nàmọ́nà ń da àwọn láàmú
3nigeria
19 Oṣù Ọ̀pẹ̀ 2018
46623582
A kò fòfin de owó naira tó ti pẹ́ ní Naijiria- CBN
3nigeria
24 Oṣù Ọ̀pẹ̀ 2019
49534082
Ọba Lamidi Adeyemi pé ọdún 48 lórí ìtẹ́
1entertainment
14 Oṣù Ṣẹ́rẹ́ 2019
46867291
Ogun Accident: FRSC ní Sokoto làwọn èrò náà ti ń bọ̀ wá sí Ijẹbú Ode
3nigeria
29 Oṣù Ṣẹ́rẹ́ 2020
51291668
Akẹ́kọ̀ọ́ ìmọ òfin ABU tí wọ́n jígbé lọnà Kaduna-Abuja ti gba ìdáǹdè -Ọlọ́pàá
3nigeria
29 Oṣù Ògún 2019
49506552
Ọ̀gá Ọlọ́pàá: Àwọn ọ̀gá ọlọ́pàá ìpínlẹ̀ ni yóò máa ṣàkósó FSARS báyìí
3nigeria
21 Oṣù Ṣẹ́rẹ́ 2019
46947255
AD,LP, fìdírẹmii lórí ẹ́jọ́ tí wọn fí takò iyansipo Sanwo Olu
4politics
17 Oṣù Òkúdu 2019
48666763
Ọ̀fẹ́ ni 'Bail': Ajulo ní ó lòdì sófin láti sanwóo béèlì fáwọn ọlọ́pàá, ẹ sọ́ra!
3nigeria
22 Oṣù Ọ̀wàrà 2019
50138320
Ìjọba àpapọ̀ Nàìjíríà fèsì sí ilẹ̀ gẹ̀ẹ́sì,EU àti Amẹ́ríkà
6world
27 Oṣù Ṣẹ́rẹ́ 2019
47018927
Tá láwọn ọba aládé àti olóṣèlú tí EFCC n wà lórí owó ìrànwọ́ N2bn ní Kwara?
4politics
29 Oṣù Agẹmọ 2019
49156034
Ìtàn Mánigbàgbé: Diipọ Fagunwa ní a le è pe bàbá òun ní ‘osó’ ìtàn àkọsílẹ̀
1entertainment
12 Oṣù Ọ̀pẹ̀ 2019
50760143
2019 Elections: PDP ní àmì pé ayé ti kọ ìjọba Buhari ní wọn ṣe ju òkúta lù wọ́n
4politics
12 Oṣù Èrèlè 2019
47208231
Oyo Tribunal: Mákindé ní àṣeyọrí òun nílé ẹjọ́ jẹ́ otítọ́ tó lékè irọ́
4politics
17 Oṣù Owewe 2019
49724391
Fásitì Ibadan: Kò sí àkẹ́kọ̀ọ́ obìnrin tí wọ́n fipá bá lòpọ̀
3nigeria
12 Oṣù Agẹmọ 2019
48965116
KogiDecides2019: Àjọ Ìsọ̀kan Yúròòpù àti Amẹ́ríkà bẹnu ẹ̀tẹ́ lu ìdìbò Kogi àti Bayelsa
4politics
18 Oṣù Bélú 2019
50463132
Tiwa Savage tọwọ́ bọ'wé àdéhùn pẹ̀lú UMG fún òkìkí orin rẹ̀
1entertainment
2 Oṣù Ẹ̀bibi 2019
48130712
Shiite: Suhaila El-Zakzaky ní ẹgbẹ́ àwọn kọ́ ló kéde àti dáwọ́ ìwọ́de dúró
3nigeria
1 Oṣù Ògún 2019
49195810
Lagos murder: Ọwọ́ ọlapàá tẹ afurasí òṣìṣẹ́ mọ̀nàmọ́ná tó gún tọkọ taya lọ́bẹ ní Ikoyi
3nigeria
10 Oṣù Ọ̀pẹ̀ 2019
50716358
2019 Elections: APC ní Amosun l‘eku ẹdá ìṣẹ̀lẹ̀ ìkọlù Buhari l'Abẹokuta
4politics
12 Oṣù Èrèlè 2019
47215957
Dino vs Adeyemi: Ìyàwó ni Adeyemi lágbo òṣèlú lọ́jọ́kọ́jọ́
4politics
2 Oṣù Ọ̀pẹ̀ 2019
50626100
Ikú Olumegbon: Ọdún mọ́kàndínlọ́gọ́ta ló lò lókè èèpẹ̀, kó tó mí kanlẹ̀
1entertainment
25 Oṣù Ẹrẹ̀nà 2019
47694435
ASUU: Adari ilé aṣòfin àgbà l'Abuja ṣèpàdé pẹ̀lú wọn lórí ááwọ̀ nípa IPPIS
3nigeria
28 Oṣù Ọ̀wàrà 2019
50204752
Lagos: Àjọ iwádìí ọrọ̀ ajé àgbáyé, EIU ní Ilu eko wà lára àwọn ìlú tó gbọ̀pọ̀ jùlọ lagbaye
3nigeria
21 Oṣù Ẹrẹ̀nà 2019
47649413
Ekiti: À máa fi ojú àfipa bọ̀mọdé lòpọ̀ hàn lóri tẹlẹfísọn
3nigeria
18 Oṣù Ẹrẹ̀nà 2019
47613367
Kí ló lè mú kí ìyá pa ọmọ rẹ̀ sè jẹ?
1entertainment
21 Oṣù Bélú 2019
50511335
Buhari: Bí kìí bá ṣe ìpàdé ìgbìmọ̀ aláṣẹ tí à ń ṣe, ìpayà kò bá bá mi kí ìgbẹ́jọ́ tó wáyé
4politics
14 Oṣù Owewe 2019
49699240
Ìtàn Mánigbàgbé: Mọrèmi Àjàṣorò fi ọmọkùnrin rẹ̀ kanṣoṣo rúbọ fún odò nítorí ìlú
1entertainment
20 Oṣù Èrèlè 2019
47302219
Offa Descendant Union: A dupẹ́ lọ́wọ́ àwọn agbófinró tó dóòlà àwọn ọmọ Ọffa lọ́wọ́ ajínigbé
3nigeria
11 Oṣù Owewe 2019
49638383
Ogoni: Ṣé nǹkan ti yàtọ̀ lẹ́yìn tí Ken Saro-Wiwa fi ẹ̀mí rẹ̀ lélẹ̀?
3nigeria
10 Oṣù Bélú 2018
46163444
2019 Elections: NCC ní ìròyìn òfégè ni pé ìjọba yóò ti afẹ́fẹ́ ìbánisọ̀rọ̀ pa lọ́jọ́ ìbò
4politics
14 Oṣù Èrèlè 2019
47222399
Adeboye: Màá fi ọlọ́pàá gbé ẹni tó bá lo fọ́tò mí sára kàlẹ́ńdà
1entertainment
9 Oṣù Ọ̀pẹ̀ 2018
46499427
Sarumi Ni obìnrin àkọ́kọ́ tí yóò gbégbá ipò gómìnà l'Ọyọ
4politics
27 Oṣù Ẹ̀bibi 2019
46910425
41 Days Fasting: Akẹ́kọ̀ọ́ kan gba ààwẹ̀ ọlọ́jọ́ 41, ó dèrò ilé ìwòsàn
3nigeria
7 Oṣù Owewe 2019
49618872
Lekki Toll Gate: Ìjọba ìpínlẹ̀ Èkó fajúro lórí ìpolówó tó ṣe àfihàn obìnrin ní ìhòòhò
3nigeria
4 Oṣù Ògún 2019
49225306
Yollywood: Odunlade Adekola àtàwọn òṣèré sinimá Yorùbá míràn tó padà lọ sí fásiti lọ kàwé
1entertainment
26 Oṣù Ṣẹ́rẹ́ 2020
51253699
Leicester best player award: Iheanacho, Ndidi yóò jọ du àmì ẹ̀yẹ Leicester City
5sport
20 Oṣù Ìgbé 2019
47996059
2019 Elections: Buhari ní wàhálà ìpolongo ìbò ló ṣèdíwọ́ wíwá síbi ìjíròrò
4politics
20 Oṣù Ṣẹ́rẹ́ 2019
46936545
Lagos Police: Àwọ̀n ọlọ́kadà 123 láti Jigawa kìí se àwọn agbésùnmọ̀mì
3nigeria
31 Oṣù Ògún 2019
49533850
Yollywood: Yomi Fabiyi ní ìwà aṣiwèrè ni bí ọlọ́pàá ṣe ń tẹ ẹ̀tọ́ ọmọnìyàn lójú, táwọn òṣèré tíátà náà ń lò nínú fíímù
1entertainment
6 Oṣù Ọ̀wàrà 2019
49950062
UK, Europe, US, Canada: Ọ̀pọ̀lọ̀pọ̀ ọkọ̀ ayókẹ́lẹ́ ló ti rì sàbẹ̀ yìnyín
6world
2 Oṣù Èrèlè 2019
47100341
Yemi Osinbajo: Ẹgbẹ́ àwọn àgbààgbà Yorùbá ní Osinbajo kò gbọdọ̀ kọ̀wé fipò sílẹ̀
4politics
9 Oṣù Bélú 2019
50357403
FIFA ban: Siasia ní kò sí ìgbà tí òun àti FIFA kò ní pàdé ní kóòtù
5sport
17 Oṣù Ògún 2019
49382553
2019 Election: Ṣé Ogboru ni ààrẹ Buhari fẹ́ fa oyè ààrẹ lé lọ́wọ́ ni?
4politics
18 Oṣù Ṣẹ́rẹ́ 2019
46908857
Malabu Deal: Ìgbẹ́jọ́ bẹ̀rẹ̀ lóri rìbá tí Eni, Mobil san fún Nàíjíríà
3nigeria
26 Oṣù Bélú 2018
46340935
2019 elections: INEC ní kò sáyè fún màjèṣín láti dìbò
4politics
23 Oṣù Èrèlè 2019
47339164
ASUU: Ìjọba ti gbẹ̀yìn ba ẹbọ jẹ lórí IPPS láti san owó oṣù
3nigeria
27 Oṣù Ṣẹ́rẹ́ 2020
51260418
2019 Election: Akala ní aráàlú kò ní kábàámọ̀ tí Adelabu bá wọlé
4politics
7 Oṣù Ẹrẹ̀nà 2019
47479340
Toyosi Arigbabuwo: Iṣẹ́ aránṣọ̀ ló ń ṣe níbẹ̀rẹ̀ kó tó yà sí iṣẹ́ tíátà
1entertainment
14 Oṣù Ṣẹ́rẹ́ 2020
51106496
Amotekun: Omi ṣì ń bẹ làmù fún ìjọba lórí Àmọ̀tẹ́kùn - Amòfin Fẹ́mi Abórìṣàdé
3nigeria
24 Oṣù Ṣẹ́rẹ́ 2020
51232886
Fayoṣe gba ibi ìjàmbá ọkọ̀ dé ìpolongo ìbò Atiku
4politics
7 Oṣù Ọ̀pẹ̀ 2018
46478777
Nigeria Police: Ọlọpàá f'ọ̀bẹ la ará ilú nífun nílùú Eko.
3nigeria
10 Oṣù Ṣẹ́rẹ́ 2020
51059139
Dino Melaye: Bí mo tilẹ̀ fìdí rẹmi, mo f'ọpẹ́ fún Ọlọ́run
4politics
11 Oṣù Ọ̀wàrà 2019
50015662
Domestic Violence: Wo ìlú tí wọ́n ti gbàgbọ́ pé bí ọkọ bá nà ẹ, ó nífẹ̀ẹ́ rẹ gan ni
6world
9 Oṣù Èrèlè 2020
51432382
Libya Returnees: Àtìpó 161 míì dari dé padà láti Libya layajọ́ ominira Naijiria
0africa
1 Oṣù Ọ̀wàrà 2019
49889165
Benue Fire: Ọkọ̀ akérò 18 àtàwọn tó ń gbọ́n epo ló forí ṣọta ìjàmbá iná
3nigeria
2 Oṣù Agẹmọ 2019
48840368
World Malaria Day:Kí gaan láwọn nkán tó n fa àìsàn ibà?
2health
25 Oṣù Ìgbé 2019
48057813
Ìtàn Mánigbàgbé: Kí ni ẹ rántí nípa Israel Adebajo, gbajúmọ́ oníṣòwò tó dá 'Stationery Stores' sílẹ̀?
1entertainment
26 Oṣù Agẹmọ 2019
49124835
Abuja Protest: À ń ṣe ìwádìí lórí àwọn obìnrin tí wọn mú nítorí aso péńpé
3nigeria
5 Oṣù Ẹ̀bibi 2019
48162546
Benue clashes: Àwọn agbébọn yìnbọn pa èèyàn mẹ́sàn án ni Benue
3nigeria
18 Oṣù Ògún 2019
49389012
NLC: Àwọn òsìsẹ́ Naijiria ló ń gba owó osù tó kéré jù!
3nigeria
23 Oṣù Ṣẹ́rẹ́ 2019
46969367
Mikel Arteta: Wọ́n ti kéde Mikel Arteta gẹ́gẹ́ bí akọ́nimọ̀ọ́gbá ikọ̀ Arsenal tuntun
5sport
20 Oṣù Ọ̀pẹ̀ 2019
50871297
Ẹ̀sùn àìmọ̀dí gbé Theophilous dọ́gbà ẹ̀wọ̀n, ìwé ẹ̀rí ìmọ̀ ìjìnlẹ̀ méjì ló gbé jáde
1entertainment
26 Oṣù Ọ̀wàrà 2019
50192647
Operation Amotekun: A ó da ọlọ́pàá agbègbè àti Amotekun papọ̀ - Ọ̀gá ọlọ́pàá Naijiria
3nigeria
13 Oṣù Èrèlè 2020
51493516
Immigration: Akẹ́kọ̀ọ́ méjì tó há sí ibùdó àtìpó ní Bosnia ti gúnlẹ̀ padà sí Nàìjíríà
6world
21 Oṣù Ọ̀pẹ̀ 2019
50877011
Naomi Adamu se àkọsílẹ̀ ìgbé ayé rẹ̀ ni àgọ́ Boko Haram
3nigeria
30 Oṣù Agẹmọ 2019
49161517
Dino Melaye ni àbímọ́ ni iṣẹ́ tíátà àti òṣèlú jẹ́ fún òun
1entertainment
14 Oṣù Ọ̀pẹ̀ 2019
50792900
Oyo government: Kí ló dé tí ọ̀rọ̀ Ìyálọ́jà àti Babalọja ń fà awuyewuye?
3nigeria
17 Oṣù Ọ̀wàrà 2019
48119148
2019 elections; INEC gba ìwé ẹ̀rí lọ́wọ́ olùdíje APC, PDP lẹ́yìn ìdìbò àpapọ̀ 2019
4politics
20 Oṣù Ẹ̀bibi 2019
48338681
Ọwọ́ ọlọ́pàá Eko tẹ ọmọ ọdún 22 tó jẹ́ olórí 'bambam' f'ẹ́gbẹ́ òkùnkùn Berry Boys
3nigeria
9 Oṣù Èrèlè 2020
51437361
Online VAT: Sísan owó orí ọjà lórí ayélujára yóò mú kí ọrọ̀ ajé rú gọ́gọ́ si
1entertainment
27 Oṣù Ògún 2019
49479923