news_title
stringlengths
23
128
label
class label
7 classes
date
stringlengths
15
18
bbc_url_id
stringlengths
8
8
2020 Countdown: Àwọn orílẹ̀-èdè tó ti ṣáájú Nàìjíríà wọ ọdún 2020
3nigeria
31 Oṣù Ọ̀pẹ̀ 2019
50959440
Ọmọ́táyọ̀ Olútóyè: Àwọn ǹkan tó yẹ kí ẹ mọ̀ nípa Ọ̀jọ̀gbọ́n obìnrin àkọ́kọ́ nínú ẹ̀kọ́ èdè Yorùbá lágbàyé
1entertainment
29 Oṣù Ògún 2019
49513702
Ikú Dagunro: Sajẹ ní èèyàn tó ṣe gbáralé ni Dagunro, ọ̀pọ̀ èèyàn ló dìde láti ara rẹ̀
1entertainment
13 Oṣù Òkúdu 2019
48623536
LASEMA: kí àwọn ará ìlú tó ba kẹ́fin oníṣẹ́ ibi tètè máa jáde sọ̀rọ̀
3nigeria
19 Oṣù Ọ̀pẹ̀ 2018
46616135
Yoruba Film: Ẹ wo ohun táwọn òṣèré tíàtà ń sọ nípa Alabi Yellow tó d'olóògbé
1entertainment
23 Oṣù Ọ̀pẹ̀ 2019
50883697
YCE Crisis: Kunle Olajide ní áwọn tó déte yíyọ òun ní ákọ̀wé YCE kò lẹ́nu ńbẹ̀
3nigeria
27 Oṣù Òkúdu 2019
48789410
Shiite: Ìjọba Kaduna ní òun yóò pe ẹjọ́ láti tako El-Zakzaky tó fẹ́ gba ìtọ́jú ní India
3nigeria
8 Oṣù Ògún 2019
49274485
Ibadan Drivers Clash: Àjọ OYRTMA sọ ohun tó fa wàhálà láàrín àwọn awakọ̀
3nigeria
23 Oṣù Ọ̀wàrà 2019
50157723
Libya Explosion: Èèyàn 44 ló bá ìṣẹ̀lẹ̀ náà rìn lápapọ̀
0africa
5 Oṣù Agẹmọ 2019
48879779
Fayemi: Ẹ̀sùn àjẹbánu àti lílo owó básubàsu la fi kàn wọn
4politics
23 Oṣù Ṣẹ́rẹ́ 2019
46969360
8th Assembly: Saraki pín owó ìyọ̀nda rẹ̀ fún ẹbí Leah Sharibu àtàwọn míì
4politics
10 Oṣù Òkúdu 2019
48576930
Ọlọpaa ni Abdullahi tó fipá bá ọmọdékùnrin méjì lò yoo foju ba ilẹ ẹjọ́
3nigeria
21 Oṣù Bélú 2018
46277688
Biafra at 50: Umar ní àwọn tó ń bèèrè fún ogun kò mọ bí ogun ṣe rí ni
3nigeria
16 Oṣù Ṣẹ́rẹ́ 2020
51137719
Amotekun: Miyetti Allah ní òun yóò péjú síbi ìpàdé ìta gbangba lọ́jọ́ Ajé láti sọ tẹnu òun
3nigeria
22 Oṣù Èrèlè 2020
51595689
HIV/AIDS: Ìjọba Nàìjíríà gbé èsì ìwadìí tuntun jáde lóríi ọwọ́jà HIV/AIDS
2health
17 Oṣù Ẹrẹ̀nà 2019
47600856
Xenophobic Attack:Àwọn ọmọ Naijiria sọ fun South Africa pé "Ó tó gẹ́"
0africa
2 Oṣù Owewe 2019
49548593
Texas Shooting: Ìsìn dàrú lẹ́yìn t'ágbébọn pàyàn méjì ní ṣọ́ọ̀ṣì
6world
30 Oṣù Ọ̀pẹ̀ 2019
50944241
Ẹbí Melaye: Ẹ̀rù ń bá wá lóri ilera Dino, ìgbésẹ̀ ọlọ́páà sì jẹ́ ìpálara fún
4politics
3 Oṣù Ṣẹ́rẹ́ 2019
46745005
Ìwé àdéhùn: Àwa olùdíje jẹ́ẹ̀jẹ́ láti se ìpolongo ìbò láì lọ́wọ́ ẹ̀sìn àti ẹ̀yà nínú
4politics
12 Oṣù Ọ̀pẹ̀ 2018
46534676
Ogun 2019: Ladi Adebutu ní ìdájọ́ iléẹjọ́ kò ní nǹkan se pẹ̀lú òun
4politics
15 Oṣù Ṣẹ́rẹ́ 2019
46881537
Kìí ṣe gbájúẹ̀ nìkan lọmọ Nàìjá ń ṣe lókè òkun, Yoruba ń mókè, wọ́n ń gbéṣẹ́ ńlá ṣe
3nigeria
30 Oṣù Ògún 2019
49521082
Ọlọ́kadà Jigawa: Ìjọba Eko ti wá mọ́lé lọ́nà àìtọ́, a fẹ́ owó ‘gbà má bínú’
3nigeria
3 Oṣù Owewe 2019
49561067
Europe Returnee: Fatmata ní oṣù mẹ́fà ni wọn fi bá òun ṣùn ní aṣálẹ̀ Sahara
6world
14 Oṣù Bélú 2019
50420358
Rice: Kò sí ìrẹsì lọjà mọ látàrí ibodè ti ìjọba tì pa - Ọlọja
3nigeria
24 Oṣù Ọ̀wàrà 2019
50172084
Owanbẹ: Gari Ijẹbu, bọ̀ọ̀lì àtàwọn oúnjẹ lágbo ayẹyẹ 'owanbẹ' báyìí
1entertainment
29 Oṣù Ẹrẹ̀nà 2019
47743952
Rwanda: Awakọ̀ 700 kò sí panpẹ òfin, 191 ṣẹwọn lórí ẹsùn wiwakọ lẹyìn tí wọ́n mọtí
0africa
2 Oṣù Ọ̀wàrà 2019
49902928
Google Map: Ànfààní wo ló wà nínú lílo ẹ̀rọ̀ ajuwe ọnà pẹ̀l'óhùn Nàìjíríà?
3nigeria
25 Oṣù Agẹmọ 2019
49108347
Aminat Abiodun: Òun ni Iyalode kẹtàlá, tó sì ń gun àkàsọ̀ láti ọdun 1971
1entertainment
9 Oṣù Ọ̀pẹ̀ 2018
46495948
Elections Update 2019: Ẹ fún wa ní ìbò wa lẹgbẹ́ PDP ń kigbe
4politics
5 Oṣù Ẹrẹ̀nà 2019
47458578
Bàbá tó pokùnso: Ọmọ ọdún mẹ́jọ ni ọmọdébìnrin tí baba rẹ̀ bá seré oge
3nigeria
17 Oṣù Ẹrẹ̀nà 2019
47600818
Abiola Ajimobi: Bàbá mi jẹ́ aránsọ, ìyá mi sì jẹ́ ọlọ́jà wóróbo
1entertainment
11 Oṣù Ìgbé 2019
47898722
Ibadan Oba Crisis: Lekan Balogun ní ìjọba kò pe àwọn sípàdé kó tó gbé ẹjọ́ kúrò nílé ẹjọ́
3nigeria
20 Oṣù Bélú 2019
50489888
SARS: Ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù Remo Stars ní ikọ̀ SARS ló pa agbábọ́ọ́lú òun
5sport
23 Oṣù Èrèlè 2020
51602625
Election Update 2019: Sowore dẹ́bi aijáde dibo àwọn èèyàn rú ìhàlẹ̀ Buhari
4politics
27 Oṣù Èrèlè 2019
47383960
Electricity tariff hike: Àfikún owó iná mọ̀nàmọ́ná dàbí jíja ọmọ Nàíjíríà lólè
3nigeria
6 Oṣù Ṣẹ́rẹ́ 2020
51004224
Election update 2019: Àgbère ẹgbẹ́ ló wà nídìí ọ̀rọ̀ Amosun àti APC - Jiti Ogunye
4politics
5 Oṣù Ẹrẹ̀nà 2019
47451741
#BeyondFakeNews: Ẹ ta kété sí ìròyìn òfégè
3nigeria
12 Oṣù Ṣẹ́rẹ́ 2019
46834230
Awakọ̀ àti ọmọ mẹta mọribọ nínú ìjàmbá ọkọ l'Eko
3nigeria
1 Oṣù Ṣẹ́rẹ́ 2019
46722891
Nigeria Election 2019: Báwo ni ìdìbò ònì yóò ṣe lọ?
4politics
23 Oṣù Èrèlè 2019
47341568
Tiamiyu Kazeem: Ọlọ́páà kò lẹ́tọ̀ọ́ láti fìyà jẹ ará ìlú tó bá wọ aṣọ ológun - Amofin
3nigeria
24 Oṣù Èrèlè 2020
51610455
Xenophobia: Àwọn ọ̀dọ́ kan ń ṣèwọ́de láti pè fún lílé àwọnjì kúrò ní South Africa
0africa
8 Oṣù Owewe 2019
49627707
#VerifiedTacha: Àwọn mánigbàgbé tí Olùdásílẹ̀ Twitter Jack Dorsey ṣé làsìkò ìrìnàjò rẹ sí Áfríkà
1entertainment
12 Oṣù Bélú 2019
50385276
Rape: Ajàfẹ́tọ̀ọ́ ẹni sọ pé inú opó ni ìyá ọmọbìnrin náà wà nígbà tí wọn fipá ba lòpọ̀
3nigeria
4 Oṣù Agẹmọ 2019
48872290
Facebook: Naijiria wà lára àwọn orílẹ̀èdè tó ní ojú òpó ayédèrú
1entertainment
17 Oṣù Ẹ̀bibi 2019
48313782
Ọkùnrin 26 tó múra bí obìnrin tó lọ àpèjẹ ọjọ́ ìbí wọ̀ gau ọlọ́pàá Sharia ní Kano
3nigeria
11 Oṣù Ọ̀pẹ̀ 2019
50734860
Oyo: Bisi Ilaka ní ìdìbò àwọn alága ìjọba ìbílẹ̀ lòdì sófin
4politics
31 Oṣù Ẹ̀bibi 2019
48477198
Òṣìṣẹ́ ìjọba ẹ̀ni ọdún mọ́kàndínláàdọ́ta pokùn so ní Ekiti
3nigeria
28 Oṣù Bélú 2018
46374754
2019 Election: Àwọn oloṣelu tó yege àti àwọn to fidirẹmi
4politics
2 Oṣù Ẹrẹ̀nà 2019
47426111
Ẹ wo ǹkan tí àwọn ènìyàn ń sọ nípa Tiwa Savage àti Wizkid tó fẹnu ko ara wọn
1entertainment
27 Oṣù Ọ̀wàrà 2019
50200661
NLC: Ìjọba àpapọ̀ ń tán wa ní sùúrù pẹ̀lú bó se dákẹ́ lórí owó osù tuntun
3nigeria
3 Oṣù Ọ̀pẹ̀ 2018
46423372
Curruption Scandal: Ọ̀gá NIMASA tẹ́lẹ̀ r'ẹ́wọ̀n ọdún méjìlélógójì he
3nigeria
4 Oṣù Òkúdu 2019
48501442
Iléeṣẹ́ ọlọ́pàá ìpínlẹ̀ Kaduna láwọn kò lè ṣọ pé èèyàn 66 kú ní Kajuru
3nigeria
17 Oṣù Èrèlè 2019
47269789
World Habitat Day: 'Ìjọba, ẹ ṣèrànwọ́ fáwọn tí kò rílé gbé ní Nàìjíríà'
6world
7 Oṣù Ọ̀wàrà 2019
49963439
Osogbo Police: Ọwọ́ tẹ ṣọ́jà mẹ́ta tó ya bo iléeṣẹ́ ọlọ́pàá, àwọn yókù sálọ
3nigeria
29 Oṣù Ọ̀wàrà 2019
50217597
Isreal Adesanya fàgbàhàn Kelvin Gastelum ni Atlanta
5sport
14 Oṣù Ìgbé 2019
47925075
Rélùwéè Eko: Alágbe tó kú náà jẹ́ ara àwọn tó ń jókòó lẹ́bàá ojú ìrìn
3nigeria
9 Oṣù Ìgbé 2019
47866943
Court of Appeal: Ilé ẹjọ́ ní òfin kò mọ Omo-Agege, Waive gẹ́gẹ́ bíi olùdíje APC ní ìpínlẹ̀ Delta
4politics
30 Oṣù Ẹrẹ̀nà 2019
47743775
Premier league: Ìjà orogún London, Arsenal ati Tottenham ranjú mọ ara wọn, ṣùgbọn iná ojú wọn kò ran tábà
5sport
1 Oṣù Owewe 2019
49541047
Kí ni àìsàn ìtọ̀ ṣúgà àti ọ̀nà tí o leè gbà dènà rẹ̀?
2health
14 Oṣù Bélú 2018
46201480
Child Abuse: Oyinye Mbadike ní ìbátan òun mu ọti yó ni òun ṣe dín dùǹdú ìyà fun
3nigeria
15 Oṣù Ògún 2019
49360497
Adeleke: APC ní ìdájọ́ ileẹjọ́ kòtẹ́milọ́rùn kò fún Adeleke ní ìrètí kankan
4politics
30 Oṣù Ẹ̀bibi 2019
48463820
Eko: Wale Oluwo ní ìdìbò abẹ́nú APC tó mẹ́hẹ l‘Eko ló fa sábàmí
4politics
5 Oṣù Ọ̀pẹ̀ 2018
46450917
Lagos/Ibadan Expressway: Èèyàn mẹ́jọ ló kù nínú ìjàmbá ọkọ̀ kìí ṣé mẹ́ẹ̀dógún
3nigeria
13 Oṣù Òkúdu 2019
48620045
Seyi Makinde: Iléẹjọ́ ní àwọn alága ìbílẹ̀ kó gbọdọ̀ gbé ìgbésẹ̀ kankan títí ìdájọ́ iléẹjọ́ Kòtẹ́milọ́rùn
4politics
30 Oṣù Agẹmọ 2019
49167846
Fake news: ìmọ̀ràn fáwọn ọmọ Nàìríjíà ṣaájú pínpín ìròyìn- Aṣòfin àgbà
3nigeria
7 Oṣù Bélú 2019
50329341
Omolola Ajayi ti bọ́ l'óko ẹrú lẹ́yìn tí ìjọba Nàìjíríà dá sí ọ̀rọ̀ rẹ̀
3nigeria
13 Oṣù Ṣẹ́rẹ́ 2020
51090477
#justiceforstephen: Ọlọ́pàá ìpínlẹ̀ Èkó láwọn ti mú afunrasí méjì tó mọ̀ nípa ikú Dókítà Stephen Urueye
3nigeria
5 Oṣù Ìgbé 2019
47831920
Exam Malpractices: Fọ́tò inú káàdì ìdánimọ̀ ló mú kí àkàrà tú sépo
3nigeria
6 Oṣù Bélú 2019
50319063
Ondo Assembly: Ejò da ìjókòó ilé rú , l'àwọn aṣòfin bá fẹsẹ̀ fẹ
3nigeria
25 Oṣù Agẹmọ 2019
49116528
Olojo festival: Buhari kan sáárá sí Ọọ̀ni, pè fún ìgbélékè àṣà adúláwọ̀
1entertainment
28 Oṣù Owewe 2019
49867490
TCN, ní kò s'óhun tí yóò ṣe iná mànàmáná ní Nàìjíríà lóní
3nigeria
13 Oṣù Ẹ̀bibi 2019
48256008
Ìjọba Kaduna: Gbogbo àwọn tó wà nídìí ìṣẹ̀lẹ̀ ìpànìyàn yóò gé ìka jẹ
3nigeria
15 Oṣù Èrèlè 2019
47260490
Ilé asòfin àpàpọ̀: Owó osù amúgbálẹ́gbẹ̀ẹ́ aṣòfin kan dín ní ₦150k sí ₦250k
3nigeria
10 Oṣù Ọ̀pẹ̀ 2018
46504196
Donkey ban: Nàìjíríà bẹ̀rẹ̀ ìgbésẹ̀ òfin láti dẹ́kun kíkó kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ lọ sí China
6world
15 Oṣù Bélú 2018
46210764
2019 elections: Ilé iṣẹ́ ológun ní ìwé òfin Nàìjíríà fàyè sílẹ̀ fáwọn láti wà níta fún àmójútó ìdìbò
4politics
8 Oṣù Ẹrẹ̀nà 2019
47498727
Immigration: Gbogbo òṣìṣẹ́wa pátá ni yóò ṣe àyẹ̀wò òògùn olóró
3nigeria
22 Oṣù Ọ̀pẹ̀ 2019
50883695
DAAR Communications: AIT, RayPower padà lẹ́yìn àṣẹ ilé ẹjọ́
1entertainment
8 Oṣù Òkúdu 2019
48553413
EKSU: Àwọn òṣìṣẹ́ tí fásitì EKSU lé fún ìgbìmọ̀ aláṣẹ ní gbèdéke ọgbọ̀n ọjọ́ láti dá wọn padà sí ẹnu iṣẹ́
3nigeria
25 Oṣù Ṣẹ́rẹ́ 2020
51247386
Ogun PDP:Buruji Kashamu kìí ṣe ọmọ ẹgbẹ́ wa- Ọlọgbọndiyan
4politics
11 Oṣù Ọ̀pẹ̀ 2018
46526675
Insecurity: Monguno ní àsìkò ti tó láti f'òpin sí Almajiri ní Nàìjíríà
3nigeria
4 Oṣù Ọ̀pẹ̀ 2019
50663730
JAMB ṣe ìdádúró lílo nọ́mbà ìdánimọ̀ fún ìdánwò àṣewọlé ọdún 2020
3nigeria
11 Oṣù Ṣẹ́rẹ́ 2020
51077537
Osun Accident: Ọkọ̀ àwọn olùjọ́sìn náà dédé yíwọ́ lọ kọ lu ògiri
3nigeria
9 Oṣù Èrèlè 2020
51435133
Ọwọ́ tẹ ọkunrìn tó n fi kẹ́míkà ṣe ìtọ́jú àìsàn jẹjẹrẹ àti ibà.
2health
24 Oṣù Ẹ̀bibi 2019
48393131
Nigeria 2019 Elections: Alága INEC, Mahmood Yakubu ní àṣẹ Ààrẹ Buhari lórí pípa ẹni tó bá jí ìbò gbé tako ohun tí òfin sọ
4politics
19 Oṣù Èrèlè 2019
47295232
APC Oyo: Àkọsílẹ̀ rere wà pé Ajimobi ni gómìnà tó dáńtọ́ jùlọ ní Ọyọ
4politics
16 Oṣù Ọ̀wàrà 2019
50066008
Komla Dumor: Solomon Serwanjja jáwé olúborí nínú Àmì ẹ̀yẹ BBC
1entertainment
30 Oṣù Owewe 2019
49868717
N37b for NASS: 'Ilé aṣòfin àgbà l'Abuja le dà wó lulẹ̀ láì ṣe àtúnṣe rẹ̀ ní kíákíá'
3nigeria
31 Oṣù Ọ̀pẹ̀ 2019
50953802
Saraki: Àwọn aṣòfin àpapọ̀ ṣ'àfihàn ìṣọ̀kan lásìkò tí jàǹdùkù jí ọ̀pá àṣẹ ilé gbé
4politics
7 Oṣù Òkúdu 2019
48552639
Shiite: Ojú Zakzaky kan ti fọ́, májèlé sì wà nínú ara rẹ̀, ìyàwó rẹ̀ kò sì le è rìn mọ́
3nigeria
5 Oṣù Ògún 2019
49232189
Sharafadeen Ali ni olùdíje sí ipò gómìnà ZLP ní ìpínlẹ̀ Ọyọ
4politics
30 Oṣù Ṣẹ́rẹ́ 2019
47026084
Catholic Church: A kò ní bó àṣírí àlùfáà tó bá bá ọmọdé lòpọ̀ mọ́
1entertainment
17 Oṣù Ọ̀pẹ̀ 2019
50828370
BBC Nigeria 2019: Àwọn èèkàn ọmọ Ogun nínú ìṣèjọba Nàìjíríà.
4politics
7 Oṣù Èrèlè 2019
47153955
Wo àwọn ohun tó yẹ kí o mọ̀ nípa DCP Kayọde Ẹgbẹdokun
3nigeria
14 Oṣù Ṣẹ́rẹ́ 2019
46860344
Italy Parliament: Ìjọba gé aṣòfin àpapọ̀ láti 630 sí 400
6world
9 Oṣù Ọ̀wàrà 2019
49986322
Iya Rainbow: Ó yẹ́ ká máa yẹ́ àwọn onítíátà sí ní ààyè, kìí ṣe òkú wọn
1entertainment
14 Oṣù Ògún 2019
49343250
Ramadan: Sultan pàṣẹ fún àwọn mùsùlùmí láti ṣ'ọdẹ òṣùpá lónìí
3nigeria
3 Oṣù Òkúdu 2019
48495384
Funke Adesiyan: Gbajúgbajà òṣèré Yollywood di olùrànlọ́wọ́ aya ààrẹ, Aisha Buhari
1entertainment
17 Oṣù Ọ̀wàrà 2019
50079397
Oyo state: 615, nọ́mbà tuntun fún ìdáàbòbò àwọn èèyàn ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ̀
3nigeria
30 Oṣù Owewe 2019
49886224
Shiite: Ẹgbẹ́ Shiite fẹ́ wọ́de ní ìrántì àwọn ọmọ ẹgbẹ́ wọn ti iléèṣẹ́ ológun Nàìjíríà pa
3nigeria
7 Oṣù Ọ̀pẹ̀ 2018
46478778
Algeria: Ààrẹ Bouteflika ti ń ṣàárẹ̀ láti ọdun márun, tó tún fẹ́ dìje padà
0africa
7 Oṣù Ẹrẹ̀nà 2019
47465683