nomiracl / data /yoruba /topics /dev.relevant.tsv
nthakur's picture
added initial training data and script
9ca02d1
raw
history blame
14.8 kB
10020#0 Odun wo ni wọn ṣe idije Olympiiki akọkọ?
10118#0 Orile ede wo ni Washington DC wà?
11164#0 Ipa wo ni Benito Mussolini se ni Ogun World War 2?
11194#0 ẹgbẹ wo ni Huey Newton da silẹ?
11419#0 Ilu wo lo tobi ju lọ ni orile-ede Poland
11610#0 Ọdún wo ni ẹlẹṣẹ ti a mọ sí Ray Robinson fi aiye silẹ?
11673#0 Ki ni oluiilu orile ede Japan?
12167#0 ọdún wo ẹlẹsẹ ti a mọ sí Dick Tiger ṣ'aláìsí?
12299#0 ilu wo lo tobi julọ ni orile-ede Mauritania?
13267#0 ta ni gomina ipinle yamoussoukro?
13308#0 kí ni olú ìlú orile ede Puerto Rico?
13499#0 Ile iwe eko giga wo ni Charles Soludo lọ?
13529#0 iru kemika wo ni won ni won fi n se batiri?
13593#0 Ki ni awon apẹrẹ kemika?
13681#0 Awọn akọrin wo ni wọn wá láti Detroit?
13888#0 ilu wo ni Lake Victoria wa?
13935#0 Awon orile ede wo ni won pe ni Balkani?
14719#0 Nibo ni ibùdó àwọn Ajagun ni ipinlẹ Borno wà?
14738#0 Ọdún wo ni wọn dá NASA silẹ?
14921#0 Kini orukọ ere ti Chris Tucker ba Jackie Chan ṣe?
15096#0 Odun wo ni Andy Ruiz ati Anthony Joshua ja?
15109#0 Ilu wo ni won bi Fyodor Dostoyevsky si?
15123#0 Omo odun meloo wo ni Nietzshe nigba to je alaga ni Yunifasiti Basel?
15124#0 ọmo orile ede wo ni John Locke?
15131#0 ọjọ meloo lo wa ninu oṣu february?
15306#0 Egbe agbaboolu wo ni Dwight Yorke gba bóòlù fún?
15329#0 Ọdún wo ni Namadi Sambo jẹ Gomina ipinle Kaduna ?
15415#0 Odun wo ni Alfred Landon je gomina ipinle Kansas?
15465#0 Asiko wo ninu ọdun lo da ju lọ lati lọ si ilu botswana?
15502#0 esin wo lo gbajumọ julọ ni orile-ede Albania ?
15508#0 Ẹsin wo lo ga ju lọ ni orile-ede Armenia?
15512#0 Awon orile ede wo lo yika Austria?
15573#0 Omo meloo ni Victoria Beckham bi fun David Beckham?
15583#0 esin wo lo gbajumọ julọ ni orile-ede India?
15770#0 Osu meloo ni Ernest Shonekan lo gege bi aare orile-ede Naijiria?
15776#0 Ede wo ni wọn sọ ni orile-ede Bhutan?
15814#0 Orile ede wo ni won ti n so ede Lingala?
15826#0 ìyàwó mélòó ni anọbi muhammad fẹ?
15848#0 Odun wo ni orile-ede Grenada gba ominira?
15863#0 ọdún wo ni wọn bí akọwe Chinua Achebe ?
15973#0 Esin wo lo gbajumo ju ni orile-ede Lituenia?
16114#0 oṣù wo ni keresimesi má ń bọ́ sí?
16313#0 Aafaa wo lo kọ Abdul Qadir Gilani ni kewu?
16336#0 Èdè wo ni àwọn ará St Kitts and Nevis n sọ?
16348#0 Egbe oloselu wo ni Boris Johnson wa pẹlu?
16352#0 èdè mélòó ni wọn sọ ni orile ede singapore?
16361#0 ọdun wo ni awọn italy fun somalia ni ominira?
16384#0 ọdún wo ni Emomali Rahmon di ààrẹ Orile ede Tajikistan?
16397#0 Ede wo ni wọn sọ ni Tunisia?
16415#0 Ki ni orukọ Pope ti o wa ni'po nisin?
16780#0 Ki ni olu-ilu ipinle Osun?
16900#0 Ilu wo lo tobi ju lọ ni ipinlẹ Anambra?
16908#0 ara ilu wo ni christopher abani?
17043#0 Ipo wo ni Raji Fashola wa labe ijọba Buhari?
17237#0 ọdún wo ni wọn kọkọ ṣe iwadi èédú ni ipinlẹ Enugu
17311#0 ipinlẹ wo ni Isiala Ngwa wa ni Nàìjíríà?
17516#0 Ati ibo ni awọn ara Oguta ti wa?
17552#0 Ipinle wo ni ilu Orlu wa?
17692#0 Ede won ni won sọ ni ipinle Plateau?
18031#0 Odun wo ni won da egbe World Health Organization silẹ?
18081#0 Ba wo ni oju ọjọ ṣe ri ni Gabon?
18270#0 Orile ede wo ni San Marino wa?
18317#0 Ta ni Aare orile-ede Zimbabwe?
18395#0 Ki ni iyato laarin UK ati Britani?
18542#0 Odun wo ni Mike Tyson ba Lennox Lewis ja?
19087#0 ọdún wo ni wọn dá ipinlẹ Nasarawa silẹ?
19105#0 Ipinlẹ wo ni a bi oloṣelu Bola Tinubu si?
19244#0 Odun wo ni Anthony Joshua di ọjọgbọn ẹlẹṣẹ?
19255#0 ara ìlú wo ni ẹlẹsẹ Andrew Tate?
19277#0 Ba wo ni oju ọjọ se ri ni ilu Miami?
19496#0 Ta ni Aarẹ orile ede Ivory Coast?
20042#0 Ede wo ni wọn sọ ni orile-ede Tanzania?
20231#0 Odun wo ni Augusto Pinochet je aare orile-ede Chile?
20612#0 Ta ni gomina ipinlẹ Taraba?
20613#0 Odun wo ni Jolly nyame je gomina ipinle taraba?
20775#0 kí ni oluilu orile-ede griisi?
20823#0 ṣe igbakeji aarẹ ma n gba owo oṣu?
20950#0 Odun wo ni Ogun Agbaye keji ti a mọ si World War 2 pari?
20961#0 Omo orile-ede wo ni osere Yvonne Nelson?
21001#0 awọn ipo wo lo ṣe pàtàkì jù lọ ní ìjọba Kanada?
21336#0 Esin wo lo gbajumọ ju ni orile-ede Amerika?
22136#0 Ibasepo wo lo wa laarin India ati Pakistan?
22351#0 Awon osere wo lo wa lati orile-ede Vietnam?
22782#0 Odun wo ni Alessandro Del Piero bẹrẹ si gba bọọlu?
22785#0 Osere wo o se fiimu Selma?
22786#0 Ọdún wo ni Pope John Paul s'alaisi?
23435#0 ọdun wo ni Julius Caesar ku?
23490#0 ilu wo lo tobi ju lo ni ipinle Tamil Nadu?
23534#0 Odun wo ni King Leopold ṣ'alaisi?
23620#0 Ki ni oruko ṣọọsi Paul Adefarasin?
23625#0 Ki ni olu-ilu orile-ede Egypt?
23682#0 ọdún wo ni wọn bẹrẹ ogun ni orile-ede Somalia?
24542#0 Odun wo ni Pope Francis ti di Pope?
24640#0 ọdun wo ni Pope John Paul ṣ'alaisi?
24860#0 Oṣù wo ni ọdún 1967 ni ogun Biafra bẹrẹ?
24913#0 Odun wo ni wọn da ẹgbẹ United Nations silẹ?
24925#0 Orile ede wo lo yege ni world cup ọdun 1986?
25355#0 Orukọ wo ni a n pe orile-ede Botswana ki wọn to yi pada?
25390#0 Ipinle meloo lo wa ni orile ede Amerika?
2560#0 Iwe wo ni akowe Chinua Achebe kọkọ kọ?
2578#0 Awon orile-ede wo lo sunmo Afghanistan?
2580#0 Awon eya wo ni won ko l'eru ju ni Afrika?
2596#0 Ki ni oluilu orile ede Albania?
26086#0 Kí ni oluilu orile-ede Finland?
2661#0 Awon iṣẹlẹ wo lo ṣẹlẹ ni Odun 1995?
27070#0 Odun wo ni won bi Otto von bismarck?
2734#0 Kí ni iye èèyàn alawọ dúdú tó wà ní orile ede Bahamas?
27390#0 bawo ni ọkọ ofurufu ṣe yára tó?
27708#0 Awon orile-ede wo lo sunmo Antigua?
27744#0 Awon awari ati iwadi wo ni Burton Richter gbe jade?
27745#0 ọmọ orile ede wo ni Samuel Peters?
27854#0 Egbe oloselu wo ni Goodluck Jonathan wa pẹlu?
27945#0 erékùṣù wo ni a ti le ri ẹranko tí a mọ sí komodo?
28208#0 ọdún wo ni wọn kọkọ bẹrẹ ẹbun Nobel ?
28245#0 Awo wo ni Akorin Kanye West kọkọ gbe jade?
28633#0 Osu wo ni odun easter ma n bọsi?
28994#0 Asiko wo ni awọn musulumi ma n ki irun ọsan?
29344#0 Ta ni o gba Ebun Nobeli fún Kemistri ọdún 2002?
29560#0 awọn awari sayensi wo ni Renato Dulbecco gbe jáde?
29679#0 Ara ilu wo ni Maurice Bishop?
3017#0 Nibo ni Naijira ni Nok wa?
30269#0 ọdún wo ni alpha conde jẹ ààrẹ Orile ede guinea?
30270#0 Ta ni aare orile ede equitorial guinea?
30627#0 ọdun wo ni ẹlẹṣẹ Joe Louis ba Max Schmeling ja?
30684#0 Ilu wo yunifasiti of Carlton wà?
30974#0 Ki ni idi ti a se n pe Lekki ni Peninsula?
31023#0 ṣe awọn Musulumi wa ni orile-ede India?
31034#0 Iwe meloo ni Mary Anne Evans kọ?
31099#0 Odun wo ni Adekunle Ajasin fi aiye silẹ?
3331#0 ọjọ meloo lo wa ninu oṣu August?
33524#0 Nibo ni poland ni ilu Krakov wa?
33551#0 Awon orile-ede wo lo sunmo Tunisia?
33553#0 Odun wo ni won Bill Gates da ile iṣẹ Microsoft silẹ?
3361#0 nọmba wo lo kere ju lọ ní mathimatiiki?
33661#0 Ọdún mélòó ni Ashley Cole ṣe gba bọọlu fún ẹgbẹ agbaboolu Chelsea?
33958#0 oniyẹyẹ wo lo gbajumọ julọ ni Naijiria?
34147#0 ọdun wo ni awọn agbabọọlu orile-ede jeman ru World cup?
3545#0 Ọmọ ìlú wo ni òṣèré Genevieve Nnaji?
35580#0 awọn ẹbun wo lo dara julọ fún ọlọjọ ibi?
35932#0 ọdún wo ni Martin Delany wá sí ilẹ abeokuta
36761#0 ọmọ orílé èdè wo ni akọrin Mya Harrison
36841#0 Ile iṣẹ iroyin wo ni Funmi Iyanda ba ṣiṣẹ?
36871#0 Iru orin wo ni Salawa Abeni kọ?
36921#0 awọn irin iṣẹ wo ni àwọn oni Sákárà ma n lo?
37045#0 Ilu wo ni wọn ti n ṣe ọtí Heineken?
37174#0 Ẹsin wo lo gbajumọ ni Orile-ede Sierra Leone?
37178#0 Awon ilu wo lo tobi julọ ni orilẹ ede Spain?
37220#0 Ede wo ni won n so ni orile-ede Spain?
37221#0 ẹsin wo lo gbajumọ ju ni orile-ede Spain?
37319#0 Ki ni iye eniyan to wa ni orile-ede Bolifia?
37639#0 ọdún wo ni won da yunifasiti Oxford silẹ?
37663#0 Ẹlẹṣẹ wo ni a mọ si Cassius Clay?
37677#0 Odun wo ni Agbaboolu Roberto Carlos fehinti?
37700#0 Irawo meloo lo wa lara aṣia orile-ede Amerika?
37746#0 Ilu wo ni wọn bi Bobby Benson si?
37764#0 Egbe oloselu wo ni Maxine Waters wa pẹlu?
38048#0 Ọdún wo ni Napoleon Bonaparte ṣ'alaisi?
38275#0 kí ni oluilu orile-ede Haiti?
3952#0 Awon orisi atomu wo lo wa?
3954#0 awọn agbara wo ni gomina ni ni orile-ede Naijiria?
4008#0 Onimọ fisisi wo lo ṣe iwadi X-ray?
4078#0 ṣe ipinle Ọṣun ni Ile Ife wa?
41815#0 Planeti meloo lo wa ni agbaye?
48995#0 kí ni o ma n fa arun Parkinson ?
49384#0 Ki ni itumo asteroidi?
5024#0 Odun wo ni won da Yunifasiti of Ife silẹ?
53825#0 kí ni orúkọ àwọn ọmọ ti anọbi Adam bi?
53850#0 Ilu wo ni won bi agbaboolu Oxlade Chamberlain si?
54114#0 Odun meloo ni Frank Lucas lo ni ewon ki o to s'alaisi?
54186#0 Odun wo ni Calvin Klein da ile iṣẹ rẹ silẹ?
54221#0 Bawo ni eeyan ṣe le kọ iṣẹ akọrin?
54493#0 ọmọ ilu wo ni baba to bi Lewis Hamilton?
54938#0 ọmọ orile ede wo ni Gloria asunmu?
54948#0 ẹbun Grammy mélòó ni Mary J Blige ti gbà?
55811#0 Ilu wo ni wọn bi alawada Eddie Murphy si?
58532#0 Ibasepo wo lo wa laarin Bill Clinton ati Monica Lewinsky?
58609#0 orile-ede wo ni ilu Birmingham wà?
58900#0 Koopu meloo ni Sir Alex Ferguson gba gẹgẹ bi monija Manchester United?
58909#0 Awon erekusu wo lo sunmo orile-ede Faranse?
59033#0 Yunifasiti wo ni wọn kọko da silẹ ni Naijiria?
59455#0 ọdún wo ni Mariah Carey kọkọ gbé àwo jáde?
59526#0 ọdun wo la da ile iṣe naijirian tẹlefisan authority silẹ?
59902#0 Ilu wo lo tobi ju ni orile-ede Korea?
60238#0 Omo orile ede wo ni Li Lianjie?
60297#0 Awọn gbajumo wo lo lọ wo ija Pacquiao ati Mayweather?
60299#0 Odun wo ni Eddie Murphy bẹrẹ si ṣe fiimu?
60314#0 Ki ni orukọ ogbontarigi oṣere ti a mo si Baba Suwe ?
60352#0 awọn iṣẹlẹ wo lo ṣẹlẹ ní ọdún 1922?
60391#0 Ki ni orukọ ile iṣẹ ti Dapo Abiodun da silẹ?
60406#0 ati ilu wo ni ede geesi ti wa ?
60435#0 Kontinenti wo ni Jamaika wa?
60451#0 Ilu wo ni won bi Victor Anichebe si?
60638#0 Ibaṣepo wo lo wa laarin Peter ati Jesu ninu Bibeli?
60675#0 Eniyan meloo lo n gbe ni Villeneuve-d'Ascq?
61003#0 ilu wo lo tibi julọ ni ipinle Bahia?
61062#0 Ki ni orukọ ẹgbẹ oloṣelu ti Herbert Macaulay da silẹ?
61263#0 Ta ni Aarẹ orile-ede Bulgaria?
61267#0 Ilu wo lo tobi ju lọ ni orile ede Bulgaria?
61282#0 Kin ni awọ asia orile-ede Bahamas?
61830#0 oṣu meloo lo wa ninu ọdun?
61865#0 Awọn oogun wo ni eeyan le lo lati fi wo aisan oju san?
61883#0 Ki lo ma n fa arun malaria?
61953#0 Awon sistemu meta wo lo wa ni ede Japanese?
62019#0 Oogun wo ni eeyan le lo fun taifọọdu?
62111#0 Ki ni o ma n fa arun Meningococcal?
62211#0 Erekuṣu wo ni a ti le ri Alangba Komodo?
62223#0 awon ẹya alangba meloo lo wa?
62234#0 awọn ẹranko wo ni wọn ma n gbe'le aiye pẹ́ jù?
62364#0 ẹranko wo lo tobi ju lọ nile aiye?
62459#0 olorin wo lo kọ "Billie Jean" ?
62473#0 Bawo ni Esther ṣe jẹ ninu bibeli?
62487#0 Ta ni ẹni tó dá Linux sílẹ̀?
62585#0 Ọsu wo ni akọkọ ninu ọdun?
62594#0 ọdún wo ni Bola Tinubu jẹ gomina Eko?
62597#0 Igba wo ni wọn ma ṣe idibo ni orile-ede Amerika?
6505#0 ọdun wo ni ọkọ ofurufu Sosoliso ja lulẹ ni Naijiria?
65770#0 Odun wo ni wọn bi elere idaraya ti Jamaika ti a mọ si Yohan Blake?
65781#0 Ki ni iye eeyan to wa ni orile-ede Taiwan?
65947#0 Yunifasiti wo ni Bukola Saraki ti ka'we?
66449#0 Omo odun meloo ni Alan Turing nigba ti o ku?
66454#0 Egbe agbaboolu wo ni Willy Caballero n gba boolu fun?
66883#0 Ara ilu wo ni Niyi Akinmolayan?
67530#0 Yunifasiti wo ni Dapo Abiodun ti ka'we?
67648#0 Ọmọ mélòó ni Odùduwà bí ?
67726#0 kí ni oluilu orile-ede South Sudan ?
67866#0 Kini oruko ṣọọsi ti David Oyedepo da silẹ?
67944#0 Ile-iwe eko giga wo ni Tam David West ti kawe?
68042#0 Ta ni ẹni tó ní ilé iṣẹ soundcity ?
68128#0 Iṣẹ wo ni Lizzy Anjorin ṣẹ?
68177#0 iru orin wo ni Fela Kuti kọ?
68257#0 Odun wo ni Frederick Fasheun ṣ'alaisi?
68332#0 Ta ni o da ilé iṣẹ Instagram silẹ?
68382#0 Odun wo ni Aremu Gbadebo je Alake?
68412#0 Ta ni o da ile iṣẹ Daar Communications silẹ?
68449#0 Bawo ni awọn Hausa ṣe n ṣe Fura ti wọn?
68452#0 Ọdún wo ni wọn da ilé iṣẹ Facebook silẹ?
68729#0 Awon eya wo ni Ghana ni won sọ ede Akan
68921#0 Odun wo ni ogun Kiriji bẹrẹ?
69129#0 Ilu wo ni wọn bí Yvonne Nelson si ?
69146#0 Iṣẹ wo ni Aisha Buhari n ṣe??
69209#0 Omo orile ede wo ni William Onyeabor?
69258#0 Ibasepo wo lo wa laarin Oluremi ati Bola Tinubu?
69260#0 ilé iṣẹ iroyin wo ni Eugenia Abu bá ṣiṣe?
69301#0 Akọwe wo lo kọ "Things fall apart"?
69308#0 ọdún wo ni oba rilwanu Akiolu di ọba eko?
69396#0 Odun wo ni Botswana gba ominira?
69434#0 Kí ni orúkọ ilé iṣẹ ti Alhaji Razaq Ọkọya da silẹ?
69691#0 oṣù wo ni àjàkálẹ̀ àrùn COVID dé Nàìjíríà?
69708#0 Orile ede wo ni àwọn Xhosa pọsi jù lọ?
70116#0 Ilu wo ni Moshood Abiola Politekniki wa?
70124#0 ọdun wo ni orile-ede Naijiria gba ominira?
70144#0 Ki ni oruko bibi osere Ade Love
70154#0 Ebun fiimu wo ni Nse Ikpe-Etim gba ni odun 2014?
70169#0 Awọn orukọ wo ni a n pe ni orukọ amutorunwa?
70186#0 Ọdún wo ni Ayo Fayose di gomina ipinlẹ Èkìtì?
70298#0 Omo ilu wo ni Kemi Adeosun?
70317#0 Ọdún wo ni òṣèré Rachel Oniga bẹrẹ sí ṣe eré itage?
70430#0 Odun wo ni Stella Obasanjo s'alaisi?
70487#0 Omo meloo ni Bose Ogulu bi?
70501#0 ọdun wo ni Teniade Aofiyebi kopa ninu fiimu Flower Girl?
70508#0 Ara ilu wo ni Lisa Omorodion?
70580#0 oṣere wo ni a mọ si Hubert Ogunde?
70588#0 awon fiimu wo ni Rosaline Meurer ti se?
70604#0 Omo orile ede wo ni Kamaru Usman?
70639#0 Ile iṣe wo ni Ugonna Umerou da silẹ?
70723#0 Ọmọ orile ede wo ni Kansiime Anne?
70727#0 onkowe wo lo kọ Igbo olodumare?
70760#0 Ibasepo wo lo wa laarin Tariro ati Emmerson Mnangagwa?
70931#0 Kontinenti wo ni Peru wa ?
71075#0 Ta ni o kọkọ jẹ aare orile ede Tunisia?
71133#0 Orile ede wo ni Kunqu Opera ti wá?
71225#0 Orile-ede wo ni wọn bi Elon Musk si?
71253#0 Awon oṣere wo lo se ere Love Castle?
71290#0 Odun wo ni Nana Akufo Addo je aare orile ede Ghana?
71301#0 Odun wo ni Erica Nlewedim kopa ninu ere Big Brother?
71355#0 Orile ede wo ni Sacramento wa?
71373#0 Orile ede wo ni ilu Ghadames wa?
7147#0 Agbegbe wo ni Eko ni Desmond Elliot n se asoju fun?
7148#0 ọdun wo ni wọn bẹrẹ Ẹbun Nobel?
9149#0 Ki ni oluilu ipinle Ọsun?
9441#0 Odun wo ni Stella Obasanjo fi aiye silẹ?
9505#0 Odun wo ni wọn bi akọrin Adekunle Gold?
9593#0 Kí ni orúkọ bibi akọrin Naira Marley?