Datasets:

Multilinguality:
multilingual
Annotations Creators:
expert-generated
ArXiv:
License:
miracl / miracl-v1.0-yo /topics /topics.miracl-v1.0-yo-test-b.tsv
Xinyu Crystina ZHANG
test-b for all and dev for surprise language
4f27ef6
10494#0 ọdun wo ni wọn pa funsho william?
10773#0 osu meloo ni oyun ma n lo nínú ikun obinrin ?
10981#0 Ki ni oruko ibilẹ ilu Port Harcourt?
11043#0 ipinlẹ wo ni gbenga Daniel ti jẹ gomina?
11172#0 Ki ni olu-ilu orile-ede Burkina-Faso?
11296#0 Ki ni oluilu Bangladesh?
11435#0 Odun wo ni Nwankwo Kanu da pọ mọ Arsenal?
11775#0 Ki ni orukọ iyawo Babatunde Fasola?
11810#0 Ki ni oluilu orile ede Bulgaria?
12525#0 Ki ni oluilu orile ede Hungari?
13297#0 ọmọ orílé ede wo ni Bill Gates ?
13310#0 kini oluilu orile-ede Paraguai?
13361#0 Ta ni o da ile iṣẹ Innoson silẹ?
13883#0 Orile ede wo ni Cape Town wa ?
13915#0 kí ni oluilu ipinle Akwa-Ibom?
14498#0 Iṣẹ wo ni Sunday Igboho n ṣe?
14783#0 Odun wo ni wọn pari ogun agbaye ikeji?
14826#0 ogagun wo lo ṣe aṣáájú àwọn ologun Biafra ni odun 1967?
14874#0 Orile ede wo ni ilu Boston wa?
15062#0 Ki ni oluilu ipinle akwa ibom?
15197#0 Iwe wo ni Ibn Battuta kọkọ kọ?
15241#0 Onimo mathematiki wo lo gbe Algebra jade?
15252#0 awọn ẹbun wo ni Roald Engelbregt gba ?
15265#0 Ta ni oba orile ede Bahrain?
15335#0 Orile ede wo ni wọn bí Kamaru Usman sí?
15367#0 ẹgbẹ olóṣèlú wo ni David Mark wa pẹlu?
15596#0 Omo orile ede wo ni Cheikh Diop?
15777#0 Ṣe orile-ede Bhutan wa ni Asia?
15787#0 Ki ni oluilu Burkina Faso?
15805#0 ọdun wo ni orile ede Kongo gba ominira?
15807#0 ipo wo ni Adolphe Muzito je labe ijoba Joseph Kabila?
15809#0 ki ni iye eeyan to wa ni orile-ede kroatia?
15882#0 obinrin alawọ dudu wo lo kọkọ yege idije Miss World?
15884#0 ọdun wo ni agbani darego yege idije Miss World?
15898#0 Ki ni wọn n pe ni Eurasia?
16001#0 kí ni olu-ilu orile-ede norway?
16007#0 Ipinle wo ni Ilu Gbongan wa?
16238#0 orile ede wo ni Ilu Madrid wa?
16281#0 Ta ni iyawo Bill Clinton?
16297#0 Èdè wo ni àwọn ará orile ede Nepal n sọ?
16373#0 Omo orile-ede wo ni onimo mathematiki Carl Friedrich?
16407#0 Odun wo ni Sultan Muhammadu Maccido ku?
16427#0 Odun wo ni won bi onisowo Efunroye Tinubu?
16770#0 Ki ni oruko bibi alawada Frank Donga?
16781#0 Ki ni oluilu ipinle Ondo?
16798#0 Odun wo ni Ekiti ati Ondo ya sọtọ?
16956#0 Tani Philip Efiong ja fun ni Ogun Biafra?
17024#0 Ipo oselu wo ni Lamidi Adesina di mu gege bi oloselu ?
17206#0 Omo ipinle wo ni Lateef Adedimeji?
17372#0 kí ni orúkọ ọba sultan ilu sókótó?
17539#0 kí ni olú ìlú ipinlẹ Rivers ?
17559#0 Ki ni olu-ilu ipinle Anambra?
17600#0 Ta ni Sultan Sokoto ni odun 2003?
18307#0 Ipinle wo ni Yunifasiti Olabisi Onabanjo wa?
18308#0 Odun wo ni Oladipo Diya je gomina ipinle Ogun l'asiko ijoba ologun?
18397#0 Odun wo ni Fidel Castro kuro lori aleefa?
18519#0 Orile ede wo ni odo Amazon wa?
18548#0 Orile-ede wo ni ilu Houston wa?
18560#0 Ta ni Aare orile-ede Amẹrika?
18642#0 kí ni oluilu orile ede Peru?
18667#0 Odun wo ni orile ede Mozambique gba ominira?
18668#0 ọdun wo ni orile-ede Mozambique gba ominira?
18809#0 Iru ounjẹ wo ni wọn ma n jẹ ni ipinle Akwa Ibom?
18859#0 Ilu wo ni won bi Serena Williams si?
18964#0 ẹgbẹ olóṣèlú wo ni Ibrahim Shekarau wa pẹlu?
19071#0 Ki ni oluilu ipinle kebbi?
19115#0 Ki ni oluilu ipinlẹ Niger?
19133#0 Odun wo ni Musilliu Haruna Ishola kọ soyoyo?
19661#0 Omo odun meloo ni Mike Tyson nigba to kọkọ gba oye heavyweight?
19971#0 Orile-ede wo ni ilu Dar es Salaam wa?
19977#0 Ise wo ni Benjamin Franklin ṣe?
20041#0 Awon orile ede wo lo yika Tanzania?
20338#0 Odun wo ni won bi onimo sayensi Thomas Edison?
20453#0 Ki ni asia orile-ede Morocco?
20573#0 Kí ni orúkọ ilé ìjọsìn David Oyedepo?
20647#0 Ibaṣepọ wo lo wa laarin Michael Jackson ati Janet Jackson ?
20692#0 Akowe wo lo kọ iwe Arrow of God?
20772#0 Odun wo ni Ogun Agbekọya bẹrẹ?
20782#0 Kí ni oluilu ipinle Jigawa?
21115#0 Kí ni oluilu orile-ede Macedonia?
21578#0 Olukowe wo lo kọ iwe Jagua Nana?
21666#0 Ọmọ ipinle wo ni Uche Jombo?
21915#0 Odun wo ni Ronald Reagan jẹ gomina California?
22043#0 Ki ni Iṣẹ igbakeji aarẹ?
22144#0 Ki ni oluilu orile ede Uganda?
22501#0 Orile ede wo ni ilu Boston wa?
22562#0 Se orile-ede Griisi dara?
22595#0 Ilu wo ni George Washington ṣe Aarẹ fun?
22677#0 Orile ede wo ni ilu Athens wa?
23142#0 Ki ni olu-ilu orile-ede Argentina?
23245#0 Awon eya wo lo tobi ju lọ ni orile-ede sierra leone?
23562#0 Omo orile ede wo ni Karl Marx?
23647#0 Kí ni oluilu orile-ede Switzerland?
25182#0 Kí ni orúkọ inagijẹ òṣèré Taiwo Hassan ?
25674#0 ọdún wo ni asiwaju Bola Tinubu kọkọ jẹ gomina ipinle Eko?
26004#0 Odun wo ni Augusto Pinochet fi aye silẹ?
26186#0 awọn orile ede wo ni àwọn komunisti pọ sí jù?
26190#0 Ara Ilu wo ni Rosa Luuxemburg?
26237#0 ọdún wo ni orile-ede Nàìjíríà di republiki?
26401#0 Ọdún wo ni Joseph Stalin fi ayé silẹ?
2749#0 Ki ni oluilu Andorra?
28166#0 egbe oṣelu wo ni Barack Obama wa pẹlu?
28630#0 Ojo melo lo wa ninu oṣu Februrari?
29343#0 Ise wo ni Ludwig Van Beethoven ṣe?
30023#0 Ile-ise wo ni Ezra Olubi da sile?
30081#0 Olorin wo lo kọ orin "African Queen"?
30366#0 Kí ni orúkọ inagijẹ onisowo orin Sean Combs ?
30369#0 Awọn ẹbun wo ni Jack Nicholson ti gba fún eré ṣíṣe?
31331#0 Pilaneeti wo lo tobi ju ̀lọ?
3171#0 Ki ni olu ilu orile-ede Cameroon?
32958#0 Ọdun wo ni wọn pari Ogun Biafra?
33282#0 Ki ni itumọ Homo Sapien?
3346#0 Ki ni iyatọ laarin "odd nomba" ati "even nomba"?
33857#0 Omo orile ede wo ni Maria Sharapova?
33976#0 Odun wo ni Joseph Stalin s'alaisi?
33997#0 ọdun wo ni wọn da orile-ede Amerika silẹ?
34105#0 ipò wo ni Teslim Elias jẹ ni International court of justice?
34138#0 Ki ni o fa iku Giordano Bruno?
35546#0 Ise wo ni Whoopi Goldberg n se?
35579#0 Ọdún wo ni Ronald Reagan jẹ ààrẹ Orile-ede Amẹrika?
35617#0 Ilu wo ni wọn bi Colin Powell si?
36817#0 Odun wo ni Bola Tinubu di Seneto?
36873#0 Iru orin wo ni Segun Adewale n kọ?
36889#0 iru orin wo ni Majek Fashek kọ?
36898#0 ile iṣẹ wo ni Peter Thiel da silẹ?
36940#0 Agbegbe wo ni Senator Abaribe n ṣe aṣoju fún?
37099#0 Ki ni Nnamdi Kanu n ja fun?
37133#0 Ki ni idi ti Suka Dimka ṣe fẹ pa Murtala?
37197#0 orile ede wo ni ilu San Francisco wa?
37479#0 Odun wo ni oṣere Moses Olaiya fi aiye silẹ?
37653#0 ọdun wo ni George washington ṣ'alaisi?
37671#0 Odun wo ni George Bush di Aare orile-ede Amerika?
37738#0 ọdún wo ni Colin Powell fi ayé silẹ?
38162#0 Agbegbe ijjọba Ibilẹ wo ni Desmond Elliot n ṣe aṣoju fun?
38221#0 Ki ni oluilu orile-ede Belarusi?
42261#0 Planeti meloo lo wa?
47009#0 Odun wo ni awon onimosayensi se awari 141 Lumen?
5126#0 Ki ni orukọ ọọni Ile Ifẹ?
5223#0 Ọdún wo ni Adesoji Aderemi jẹ Ọọni Ile Ifẹ?
53718#0 Odun wo ni Chang Myon je Minisita orile-ede Korea
53740#0 Kí ni oluilu orile-ede Kenya?
53890#0 ẹgbẹ oloṣelu wo ni Corey Booker wa pẹlu?
5392#0 Odun wo ni Olagunsoye Oyinlola di gomina Osun?
53994#0 Ta ni aare Egypti ni ọdun 2010?
54187#0 Kí ni orúkọ inagijẹ Andre Young ?
54188#0 Ki ni orukọ akọrin Curtis Jackson?
54270#0 Iṣẹ wo ni Rosa Parks ṣe?
54280#0 awọn Orile ede wo ni wọn ti n sọ Swahili?
54886#0 ẹkọ wo ni a le mu lo lati aye Jésù kristi?
55834#0 Odun wo ni Nelson Mandela kuro ni ẹwọn?
58528#0 Iṣẹ wo ni Margaret Etim n ṣe?
58529#0 Ta ni Aarẹ orile-ede Russia?
58653#0 Akorin wo lo kọ "Billie Jean" ?
59313#0 Odun wo ni Sloane Stephens yege US open?
59530#0 Odun wo ni Gloria Macapagal di aare orile ede Fillipines?
59753#0 iru metali wo ni aluminiomu?
59915#0 ọdun wo Saddam Hussein ṣe alaisi?
59947#0 Ati orile ede wo ni Reggae ti wa?
60031#0 Iru orin wo ni John Lennon kọ?
60042#0 Awon orile ede wo lo sunmo Rọṣia?
60106#0 Ki ni orukọ inagije Charles Olumọ?
60184#0 Ilu wo ni wọn bi Serena Williams si?
60571#0 Odun wo ni won bi onimo sayensi Isaac Newton?
60777#0 ọmọ ìlú wo ni Linda Ejiofor?
61172#0 Ki ni inagijẹ Dwayne Carter ?
61423#0 ọdun wo ni wọn bi aarẹ Muhammadu Buhari?
61829#0 ki ni o ma n fa arun Onchocerciasis?
61835#0 Odun wo ni Cassius Clay yi oruko si Muhammed Ali?
61882#0 Orile ede wo ni Tenerife wa?
62015#0 kí ni o ma n fa arun ọpọlọ?
62016#0 Oogun wo ni eeyan le lo lati fi pa kokoro?
62175#0 kí ni o ma n fa arun ọpọlọ?
62192#0 Ẹbun fiimu mélòó ni Stephen Spielberg ti gba ?
62295#0 idile wo ni Awujalẹ Sikiru Adetona ti wá?
62300#0 ọdun wo ni wọn da ẹgbẹ PDP silẹ?
62444#0 Odun wo ni Lateef Adedimeji bẹrẹ si ṣe fiimu?
62453#0 Awon aami wo lo ma n han wipe obinrin ti ni oyun?
65763#0 kí ni oluilu orile-ede Gambia ?
65784#0 Awo meloo ni Sikiru Ayinde Barrister ṣe ki o to ku?
65842#0 ọdún wo ni akorin Victor Olaiya ṣ'alaisi
66100#0 Ki ni oruko ile-ise tI Sean Combs da sile?
66113#0 Ipinle wo ni Aliyu Wamakko ti jẹ gomina?
66437#0 ọmọ ilu wo ni Lawrence Anini?
66876#0 Awon tira wo ni Sheik Adam Al Ilory kọ?
66945#0 ọdún wo ni wọn pa Tafawa Balewa?
67007#0 bawo ni moremi ṣe tú àṣírí àwọn ará Igbo?
67317#0 Ta ni ẹni to kọ fiimu Ovy's voice?
67362#0 Odun wo ni 9ice gbe awo Gongo Aso jade?
67416#0 Ati ibo ni Aṣọ Ofi ti wa?
67527#0 Yunifasiti wo ni Funsho Williams ti kàwé?
67557#0 ile-ise wo ni Tara Fela-Durotoye da silẹ?
67562#0 Ọdún wo ni Wahab Folawiyo fi aiyé silẹ?
67610#0 Ki ni oluilu orile-ede Kenya?
67616#0 ọjọ wo ni Valentine bọ si?
67649#0 Odun wo ni won da OGBC silẹ?
67675#0 Awọn orile ede wo ni wọn ti n sọ Urdu?
67686#0 Awon irin ise wo ni akorin Prince lo?
67688#0 ọdún wo ni akọrin Fatai Rolling Dollar ṣ'àláìsí?
67760#0 Ilu wo ni won bi Immanuella Samueli si?
67764#0 Ọdún wo ni Chioma Ajunwa gba ẹbun ni ìdíje òlímpíkì?
67775#0 Ki lo pa Samuel Okwaraji?
67786#0 Odun wo ni Gbenga Daniel je gomina ipinlẹ Ogun?
67886#0 Ta ni ọba awọn ogu ni Badagry?
67907#0 Ki ni oruko iyawo Odunlade Adekola?
67942#0 Ipò wo ni Surajudeen Ajibola jẹ ni ipinlẹ Ọsun ?
67949#0 Ọdún wo ni Haruna Ìṣọ̀lá fi aiyé silẹ?
67956#0 yunifasiti wo ni gomina Dapo Abiodun ti kàwé?
67961#0 Odun wo ni olorin tupac shakur s'alaisi?
67991#0 ipo wo ni Robert Adeyinka je ni Western Region
68015#0 kí ni orúkọ ìyàwó Yemi Osinbajo?
68024#0 Ta ni Akran ilu Badagry?
68035#0 ilé iṣẹ wo ni Tony Elumelu da silẹ?
68047#0 Ọdún wo ni George Weah di ààrẹ orile ede Liberia?
68053#0 ọdún wo ni Bukky Wright bẹrẹ sí ṣe eré itage?
68058#0 Ta ni Baba Kunle Afolayan?
68059#0 ibaṣepọ wo lo wa laarin Gabriel ati Kunle Afolayan?
68234#0 Odun wo ni won da ile ifowoppamo Wema silẹ?
68240#0 Awon ile-ise wo ni Mark Zuckerberg da sile?
68242#0 Àwọn Gómìnà wo lo da ẹgbẹ amọtẹkun silẹ?
68250#0 awọn wo lo ko samuel crowther l'ẹ́rú?
68301#0 Kí ni èèyàn lè fi ata ṣọ̀mbọ̀ sè?
68376#0 Ipinle wo ni Samuel Ortom ti je gomina?
68427#0 kí ni olúìlú ìpínlẹ̀ Abia?
68435#0 Orile ede wo ni ilu Phoenix wa ?
68664#0 Ki ni o fa iku Tolulope Arotile?
68728#0 nibo ni abule faransé wa ni Badagry?
68737#0 Ki ni awon aami wipe eeyan ti ni ni arun Coronavirus?
68841#0 Ta ni oludari NCDC?
68861#0 Ọjọ meloo lo wa ninu oṣu Februrari?
68882#0 Odun wo ni Kemi Adetiba gbe fiimu King of Boys jade?
69261#0 Ile iroyin wo ni Aisha Falode ba ṣiṣẹ?
69404#0 Ki ni orukọ abisọ alakitiyan Malik El Shabazz?
69661#0 Ki ni orukọ abisọ Burna Boy?
69674#0 Ki ni a n pe ni pythagoras theorem ni Matimatiki?
69736#0 ati ilu wo ni COVID 19 ti kọkọ bẹrẹ?
69944#0 Ile-ise wo ni Bode Akindele da silẹ?
70088#0 olorin wo lo ko "African Queen" ?
70147#0 Fiimu wo ni Rahama Sadau ṣe pẹlu Ali Nuhu?
70174#0 ere mélòó ni òṣèré eniola ajao ti ṣe?
70219#0 Iṣẹ wo ni Sandra Ezekwesili ń ṣe?
70236#0 Odun wo ni Mike Bamiloye da Mount Zion sile?
70265#0 Oye wo ni fi Gani Adams jẹ?
70287#0 ere wo ni Bukky Ajayi kọkọ gbe jade?
70355#0 Ara ìlú wo ni Ààfáà Muyideen Bello?
70363#0 Ta ni ọkọ Thelma Okoduwa?
70419#0 Ipinle wo ni Yunifasiti Ahmadu Bello wa?
70433#0 Ise wo ni Margaret Etim n ṣe?
70450#0 Kí ni orúkọ inagijẹ òṣèré tí a mọ sí Taiwo Hassan?
70460#0 Ile-iwe ko giga ẹwo ni Yvonne Orji ti ka'we?
70493#0 Ipo wo ni won fi Kemi Adeosun si labe ijoba Muhammadu Buhari
70503#0 Ilu wo ni won bi Agnes Osazuwa si?
70557#0 Ede wo ni wọn sọ ni orile-ede Burkina?
70571#0 Omo ilu wo ni Mercy Johnson?
70576#0 Ipinle wo ni Ibrahim Shekarau ti jẹ gomina?
70598#0 ọdún wo ni Ogun àdùbí bẹrẹ?
70614#0 Odun wo ni Chioma Ajunwa yege ni idije olympiiki?
70629#0 Fiimu meloo ni Ini Ikpe ti ṣe?
70633#0 ọdún wo ni akọwe Frances Welsing fi aiyé silẹ?
70656#0 Orile ede wo ni Marina Niava to wa?
70693#0 Ọdún wo ni Leopold Senghor di ààrẹ orile-ede Senegal?
70729#0 Ta ni o se oludari fiimu Mionga ki Obo?
70783#0 ọdún wo ni wọn bí Anọbi Muhammad?
70918#0 Ki ni orukọ inagije Temilade Openiyi?
70933#0 Ẹgbẹ olóṣèlú wo ni Adeniran Ogunsanya bá ṣe?
70964#0 Odun wo ni Akiwunmi Ambode jẹ gomina ipinlẹ Eko?
70974#0 Ta ni o da ile iṣẹ Mainframe silẹ?
70993#0 ipò ìjọba wo ni Femi Adesina wa labẹ ijoba Aare Buhari?
70994#0 Orile ede wo lo yege idije World Cup ti 2006?
71068#0 Awọn nkan wo ni wọn fi n ṣe Baba Ghanoush?
71092#0 Awo wo ni Temi Dee kọkọ gbé jade?
71178#0 Ipinle wo ni Ayodele Fayọse ti ṣe gomina?
71200#0 Ọdún wo ni Ezra Olubi da ilé iṣẹ Paystack silẹ?
71202#0 Iṣẹ wo ni Tiwalola Olanubi n ṣe?
71220#0 yunifasiti wo ni denrele ti kàwé?
71252#0 ki ni anfani ere idaraya?
71280#0 Ta ni ọkọ Naa Ashorkor?
71282#0 Ọdún wo ni ọgbẹni Rauf Aregbesola jẹ gomina ipinlẹ Ọsun?
71307#0 ọdún wo ni Michael Jackson gbe awo Thriller jáde?
71352#0 konsonanti mélòó ló wà nínú èdè Yorùbá?
71424#0 Odun wo ni Oluwaseun Osewa da Nairaland silẹ?
71511#0 oṣu wo ni odun 1999 ni Olusegun Obasanajo di Aarẹ orile ede Naijiria?
71529#0 Odun wo ni Vivica Fox bẹrẹ si ṣe ere itage?
71554#0 Odun wo ni Facebook ra Whatsapp?
71569#0 Odun wo ni arun coronavirus bẹrẹ?
7183#0 orile ede wo ni odo mississipi wa?
7208#0 Ọjọ mélòó ló wà nínú oṣù Dìsẹ́mbà?
7523#0 Kí ni orúkọ abisọ Kwame Ture?
8837#0 ẹgbẹ oloṣelu wo ni Boris Johnson wa pẹlu?