10494#0 ọdun wo ni wọn pa funsho william? | |
10773#0 osu meloo ni oyun ma n lo nínú ikun obinrin ? | |
10981#0 Ki ni oruko ibilẹ ilu Port Harcourt? | |
11043#0 ipinlẹ wo ni gbenga Daniel ti jẹ gomina? | |
11172#0 Ki ni olu-ilu orile-ede Burkina-Faso? | |
11296#0 Ki ni oluilu Bangladesh? | |
11435#0 Odun wo ni Nwankwo Kanu da pọ mọ Arsenal? | |
11775#0 Ki ni orukọ iyawo Babatunde Fasola? | |
11810#0 Ki ni oluilu orile ede Bulgaria? | |
12525#0 Ki ni oluilu orile ede Hungari? | |
13297#0 ọmọ orílé ede wo ni Bill Gates ? | |
13310#0 kini oluilu orile-ede Paraguai? | |
13361#0 Ta ni o da ile iṣẹ Innoson silẹ? | |
13883#0 Orile ede wo ni Cape Town wa ? | |
13915#0 kí ni oluilu ipinle Akwa-Ibom? | |
14498#0 Iṣẹ wo ni Sunday Igboho n ṣe? | |
14783#0 Odun wo ni wọn pari ogun agbaye ikeji? | |
14826#0 ogagun wo lo ṣe aṣáájú àwọn ologun Biafra ni odun 1967? | |
14874#0 Orile ede wo ni ilu Boston wa? | |
15062#0 Ki ni oluilu ipinle akwa ibom? | |
15197#0 Iwe wo ni Ibn Battuta kọkọ kọ? | |
15241#0 Onimo mathematiki wo lo gbe Algebra jade? | |
15252#0 awọn ẹbun wo ni Roald Engelbregt gba ? | |
15265#0 Ta ni oba orile ede Bahrain? | |
15335#0 Orile ede wo ni wọn bí Kamaru Usman sí? | |
15367#0 ẹgbẹ olóṣèlú wo ni David Mark wa pẹlu? | |
15596#0 Omo orile ede wo ni Cheikh Diop? | |
15777#0 Ṣe orile-ede Bhutan wa ni Asia? | |
15787#0 Ki ni oluilu Burkina Faso? | |
15805#0 ọdun wo ni orile ede Kongo gba ominira? | |
15807#0 ipo wo ni Adolphe Muzito je labe ijoba Joseph Kabila? | |
15809#0 ki ni iye eeyan to wa ni orile-ede kroatia? | |
15882#0 obinrin alawọ dudu wo lo kọkọ yege idije Miss World? | |
15884#0 ọdun wo ni agbani darego yege idije Miss World? | |
15898#0 Ki ni wọn n pe ni Eurasia? | |
16001#0 kí ni olu-ilu orile-ede norway? | |
16007#0 Ipinle wo ni Ilu Gbongan wa? | |
16238#0 orile ede wo ni Ilu Madrid wa? | |
16281#0 Ta ni iyawo Bill Clinton? | |
16297#0 Èdè wo ni àwọn ará orile ede Nepal n sọ? | |
16373#0 Omo orile-ede wo ni onimo mathematiki Carl Friedrich? | |
16407#0 Odun wo ni Sultan Muhammadu Maccido ku? | |
16427#0 Odun wo ni won bi onisowo Efunroye Tinubu? | |
16770#0 Ki ni oruko bibi alawada Frank Donga? | |
16781#0 Ki ni oluilu ipinle Ondo? | |
16798#0 Odun wo ni Ekiti ati Ondo ya sọtọ? | |
16956#0 Tani Philip Efiong ja fun ni Ogun Biafra? | |
17024#0 Ipo oselu wo ni Lamidi Adesina di mu gege bi oloselu ? | |
17206#0 Omo ipinle wo ni Lateef Adedimeji? | |
17372#0 kí ni orúkọ ọba sultan ilu sókótó? | |
17539#0 kí ni olú ìlú ipinlẹ Rivers ? | |
17559#0 Ki ni olu-ilu ipinle Anambra? | |
17600#0 Ta ni Sultan Sokoto ni odun 2003? | |
18307#0 Ipinle wo ni Yunifasiti Olabisi Onabanjo wa? | |
18308#0 Odun wo ni Oladipo Diya je gomina ipinle Ogun l'asiko ijoba ologun? | |
18397#0 Odun wo ni Fidel Castro kuro lori aleefa? | |
18519#0 Orile ede wo ni odo Amazon wa? | |
18548#0 Orile-ede wo ni ilu Houston wa? | |
18560#0 Ta ni Aare orile-ede Amẹrika? | |
18642#0 kí ni oluilu orile ede Peru? | |
18667#0 Odun wo ni orile ede Mozambique gba ominira? | |
18668#0 ọdun wo ni orile-ede Mozambique gba ominira? | |
18809#0 Iru ounjẹ wo ni wọn ma n jẹ ni ipinle Akwa Ibom? | |
18859#0 Ilu wo ni won bi Serena Williams si? | |
18964#0 ẹgbẹ olóṣèlú wo ni Ibrahim Shekarau wa pẹlu? | |
19071#0 Ki ni oluilu ipinle kebbi? | |
19115#0 Ki ni oluilu ipinlẹ Niger? | |
19133#0 Odun wo ni Musilliu Haruna Ishola kọ soyoyo? | |
19661#0 Omo odun meloo ni Mike Tyson nigba to kọkọ gba oye heavyweight? | |
19971#0 Orile-ede wo ni ilu Dar es Salaam wa? | |
19977#0 Ise wo ni Benjamin Franklin ṣe? | |
20041#0 Awon orile ede wo lo yika Tanzania? | |
20338#0 Odun wo ni won bi onimo sayensi Thomas Edison? | |
20453#0 Ki ni asia orile-ede Morocco? | |
20573#0 Kí ni orúkọ ilé ìjọsìn David Oyedepo? | |
20647#0 Ibaṣepọ wo lo wa laarin Michael Jackson ati Janet Jackson ? | |
20692#0 Akowe wo lo kọ iwe Arrow of God? | |
20772#0 Odun wo ni Ogun Agbekọya bẹrẹ? | |
20782#0 Kí ni oluilu ipinle Jigawa? | |
21115#0 Kí ni oluilu orile-ede Macedonia? | |
21578#0 Olukowe wo lo kọ iwe Jagua Nana? | |
21666#0 Ọmọ ipinle wo ni Uche Jombo? | |
21915#0 Odun wo ni Ronald Reagan jẹ gomina California? | |
22043#0 Ki ni Iṣẹ igbakeji aarẹ? | |
22144#0 Ki ni oluilu orile ede Uganda? | |
22501#0 Orile ede wo ni ilu Boston wa? | |
22562#0 Se orile-ede Griisi dara? | |
22595#0 Ilu wo ni George Washington ṣe Aarẹ fun? | |
22677#0 Orile ede wo ni ilu Athens wa? | |
23142#0 Ki ni olu-ilu orile-ede Argentina? | |
23245#0 Awon eya wo lo tobi ju lọ ni orile-ede sierra leone? | |
23562#0 Omo orile ede wo ni Karl Marx? | |
23647#0 Kí ni oluilu orile-ede Switzerland? | |
25182#0 Kí ni orúkọ inagijẹ òṣèré Taiwo Hassan ? | |
25674#0 ọdún wo ni asiwaju Bola Tinubu kọkọ jẹ gomina ipinle Eko? | |
26004#0 Odun wo ni Augusto Pinochet fi aye silẹ? | |
26186#0 awọn orile ede wo ni àwọn komunisti pọ sí jù? | |
26190#0 Ara Ilu wo ni Rosa Luuxemburg? | |
26237#0 ọdún wo ni orile-ede Nàìjíríà di republiki? | |
26401#0 Ọdún wo ni Joseph Stalin fi ayé silẹ? | |
2749#0 Ki ni oluilu Andorra? | |
28166#0 egbe oṣelu wo ni Barack Obama wa pẹlu? | |
28630#0 Ojo melo lo wa ninu oṣu Februrari? | |
29343#0 Ise wo ni Ludwig Van Beethoven ṣe? | |
30023#0 Ile-ise wo ni Ezra Olubi da sile? | |
30081#0 Olorin wo lo kọ orin "African Queen"? | |
30366#0 Kí ni orúkọ inagijẹ onisowo orin Sean Combs ? | |
30369#0 Awọn ẹbun wo ni Jack Nicholson ti gba fún eré ṣíṣe? | |
31331#0 Pilaneeti wo lo tobi ju ̀lọ? | |
3171#0 Ki ni olu ilu orile-ede Cameroon? | |
32958#0 Ọdun wo ni wọn pari Ogun Biafra? | |
33282#0 Ki ni itumọ Homo Sapien? | |
3346#0 Ki ni iyatọ laarin "odd nomba" ati "even nomba"? | |
33857#0 Omo orile ede wo ni Maria Sharapova? | |
33976#0 Odun wo ni Joseph Stalin s'alaisi? | |
33997#0 ọdun wo ni wọn da orile-ede Amerika silẹ? | |
34105#0 ipò wo ni Teslim Elias jẹ ni International court of justice? | |
34138#0 Ki ni o fa iku Giordano Bruno? | |
35546#0 Ise wo ni Whoopi Goldberg n se? | |
35579#0 Ọdún wo ni Ronald Reagan jẹ ààrẹ Orile-ede Amẹrika? | |
35617#0 Ilu wo ni wọn bi Colin Powell si? | |
36817#0 Odun wo ni Bola Tinubu di Seneto? | |
36873#0 Iru orin wo ni Segun Adewale n kọ? | |
36889#0 iru orin wo ni Majek Fashek kọ? | |
36898#0 ile iṣẹ wo ni Peter Thiel da silẹ? | |
36940#0 Agbegbe wo ni Senator Abaribe n ṣe aṣoju fún? | |
37099#0 Ki ni Nnamdi Kanu n ja fun? | |
37133#0 Ki ni idi ti Suka Dimka ṣe fẹ pa Murtala? | |
37197#0 orile ede wo ni ilu San Francisco wa? | |
37479#0 Odun wo ni oṣere Moses Olaiya fi aiye silẹ? | |
37653#0 ọdun wo ni George washington ṣ'alaisi? | |
37671#0 Odun wo ni George Bush di Aare orile-ede Amerika? | |
37738#0 ọdún wo ni Colin Powell fi ayé silẹ? | |
38162#0 Agbegbe ijjọba Ibilẹ wo ni Desmond Elliot n ṣe aṣoju fun? | |
38221#0 Ki ni oluilu orile-ede Belarusi? | |
42261#0 Planeti meloo lo wa? | |
47009#0 Odun wo ni awon onimosayensi se awari 141 Lumen? | |
5126#0 Ki ni orukọ ọọni Ile Ifẹ? | |
5223#0 Ọdún wo ni Adesoji Aderemi jẹ Ọọni Ile Ifẹ? | |
53718#0 Odun wo ni Chang Myon je Minisita orile-ede Korea | |
53740#0 Kí ni oluilu orile-ede Kenya? | |
53890#0 ẹgbẹ oloṣelu wo ni Corey Booker wa pẹlu? | |
5392#0 Odun wo ni Olagunsoye Oyinlola di gomina Osun? | |
53994#0 Ta ni aare Egypti ni ọdun 2010? | |
54187#0 Kí ni orúkọ inagijẹ Andre Young ? | |
54188#0 Ki ni orukọ akọrin Curtis Jackson? | |
54270#0 Iṣẹ wo ni Rosa Parks ṣe? | |
54280#0 awọn Orile ede wo ni wọn ti n sọ Swahili? | |
54886#0 ẹkọ wo ni a le mu lo lati aye Jésù kristi? | |
55834#0 Odun wo ni Nelson Mandela kuro ni ẹwọn? | |
58528#0 Iṣẹ wo ni Margaret Etim n ṣe? | |
58529#0 Ta ni Aarẹ orile-ede Russia? | |
58653#0 Akorin wo lo kọ "Billie Jean" ? | |
59313#0 Odun wo ni Sloane Stephens yege US open? | |
59530#0 Odun wo ni Gloria Macapagal di aare orile ede Fillipines? | |
59753#0 iru metali wo ni aluminiomu? | |
59915#0 ọdun wo Saddam Hussein ṣe alaisi? | |
59947#0 Ati orile ede wo ni Reggae ti wa? | |
60031#0 Iru orin wo ni John Lennon kọ? | |
60042#0 Awon orile ede wo lo sunmo Rọṣia? | |
60106#0 Ki ni orukọ inagije Charles Olumọ? | |
60184#0 Ilu wo ni wọn bi Serena Williams si? | |
60571#0 Odun wo ni won bi onimo sayensi Isaac Newton? | |
60777#0 ọmọ ìlú wo ni Linda Ejiofor? | |
61172#0 Ki ni inagijẹ Dwayne Carter ? | |
61423#0 ọdun wo ni wọn bi aarẹ Muhammadu Buhari? | |
61829#0 ki ni o ma n fa arun Onchocerciasis? | |
61835#0 Odun wo ni Cassius Clay yi oruko si Muhammed Ali? | |
61882#0 Orile ede wo ni Tenerife wa? | |
62015#0 kí ni o ma n fa arun ọpọlọ? | |
62016#0 Oogun wo ni eeyan le lo lati fi pa kokoro? | |
62175#0 kí ni o ma n fa arun ọpọlọ? | |
62192#0 Ẹbun fiimu mélòó ni Stephen Spielberg ti gba ? | |
62295#0 idile wo ni Awujalẹ Sikiru Adetona ti wá? | |
62300#0 ọdun wo ni wọn da ẹgbẹ PDP silẹ? | |
62444#0 Odun wo ni Lateef Adedimeji bẹrẹ si ṣe fiimu? | |
62453#0 Awon aami wo lo ma n han wipe obinrin ti ni oyun? | |
65763#0 kí ni oluilu orile-ede Gambia ? | |
65784#0 Awo meloo ni Sikiru Ayinde Barrister ṣe ki o to ku? | |
65842#0 ọdún wo ni akorin Victor Olaiya ṣ'alaisi | |
66100#0 Ki ni oruko ile-ise tI Sean Combs da sile? | |
66113#0 Ipinle wo ni Aliyu Wamakko ti jẹ gomina? | |
66437#0 ọmọ ilu wo ni Lawrence Anini? | |
66876#0 Awon tira wo ni Sheik Adam Al Ilory kọ? | |
66945#0 ọdún wo ni wọn pa Tafawa Balewa? | |
67007#0 bawo ni moremi ṣe tú àṣírí àwọn ará Igbo? | |
67317#0 Ta ni ẹni to kọ fiimu Ovy's voice? | |
67362#0 Odun wo ni 9ice gbe awo Gongo Aso jade? | |
67416#0 Ati ibo ni Aṣọ Ofi ti wa? | |
67527#0 Yunifasiti wo ni Funsho Williams ti kàwé? | |
67557#0 ile-ise wo ni Tara Fela-Durotoye da silẹ? | |
67562#0 Ọdún wo ni Wahab Folawiyo fi aiyé silẹ? | |
67610#0 Ki ni oluilu orile-ede Kenya? | |
67616#0 ọjọ wo ni Valentine bọ si? | |
67649#0 Odun wo ni won da OGBC silẹ? | |
67675#0 Awọn orile ede wo ni wọn ti n sọ Urdu? | |
67686#0 Awon irin ise wo ni akorin Prince lo? | |
67688#0 ọdún wo ni akọrin Fatai Rolling Dollar ṣ'àláìsí? | |
67760#0 Ilu wo ni won bi Immanuella Samueli si? | |
67764#0 Ọdún wo ni Chioma Ajunwa gba ẹbun ni ìdíje òlímpíkì? | |
67775#0 Ki lo pa Samuel Okwaraji? | |
67786#0 Odun wo ni Gbenga Daniel je gomina ipinlẹ Ogun? | |
67886#0 Ta ni ọba awọn ogu ni Badagry? | |
67907#0 Ki ni oruko iyawo Odunlade Adekola? | |
67942#0 Ipò wo ni Surajudeen Ajibola jẹ ni ipinlẹ Ọsun ? | |
67949#0 Ọdún wo ni Haruna Ìṣọ̀lá fi aiyé silẹ? | |
67956#0 yunifasiti wo ni gomina Dapo Abiodun ti kàwé? | |
67961#0 Odun wo ni olorin tupac shakur s'alaisi? | |
67991#0 ipo wo ni Robert Adeyinka je ni Western Region | |
68015#0 kí ni orúkọ ìyàwó Yemi Osinbajo? | |
68024#0 Ta ni Akran ilu Badagry? | |
68035#0 ilé iṣẹ wo ni Tony Elumelu da silẹ? | |
68047#0 Ọdún wo ni George Weah di ààrẹ orile ede Liberia? | |
68053#0 ọdún wo ni Bukky Wright bẹrẹ sí ṣe eré itage? | |
68058#0 Ta ni Baba Kunle Afolayan? | |
68059#0 ibaṣepọ wo lo wa laarin Gabriel ati Kunle Afolayan? | |
68234#0 Odun wo ni won da ile ifowoppamo Wema silẹ? | |
68240#0 Awon ile-ise wo ni Mark Zuckerberg da sile? | |
68242#0 Àwọn Gómìnà wo lo da ẹgbẹ amọtẹkun silẹ? | |
68250#0 awọn wo lo ko samuel crowther l'ẹ́rú? | |
68301#0 Kí ni èèyàn lè fi ata ṣọ̀mbọ̀ sè? | |
68376#0 Ipinle wo ni Samuel Ortom ti je gomina? | |
68427#0 kí ni olúìlú ìpínlẹ̀ Abia? | |
68435#0 Orile ede wo ni ilu Phoenix wa ? | |
68664#0 Ki ni o fa iku Tolulope Arotile? | |
68728#0 nibo ni abule faransé wa ni Badagry? | |
68737#0 Ki ni awon aami wipe eeyan ti ni ni arun Coronavirus? | |
68841#0 Ta ni oludari NCDC? | |
68861#0 Ọjọ meloo lo wa ninu oṣu Februrari? | |
68882#0 Odun wo ni Kemi Adetiba gbe fiimu King of Boys jade? | |
69261#0 Ile iroyin wo ni Aisha Falode ba ṣiṣẹ? | |
69404#0 Ki ni orukọ abisọ alakitiyan Malik El Shabazz? | |
69661#0 Ki ni orukọ abisọ Burna Boy? | |
69674#0 Ki ni a n pe ni pythagoras theorem ni Matimatiki? | |
69736#0 ati ilu wo ni COVID 19 ti kọkọ bẹrẹ? | |
69944#0 Ile-ise wo ni Bode Akindele da silẹ? | |
70088#0 olorin wo lo ko "African Queen" ? | |
70147#0 Fiimu wo ni Rahama Sadau ṣe pẹlu Ali Nuhu? | |
70174#0 ere mélòó ni òṣèré eniola ajao ti ṣe? | |
70219#0 Iṣẹ wo ni Sandra Ezekwesili ń ṣe? | |
70236#0 Odun wo ni Mike Bamiloye da Mount Zion sile? | |
70265#0 Oye wo ni fi Gani Adams jẹ? | |
70287#0 ere wo ni Bukky Ajayi kọkọ gbe jade? | |
70355#0 Ara ìlú wo ni Ààfáà Muyideen Bello? | |
70363#0 Ta ni ọkọ Thelma Okoduwa? | |
70419#0 Ipinle wo ni Yunifasiti Ahmadu Bello wa? | |
70433#0 Ise wo ni Margaret Etim n ṣe? | |
70450#0 Kí ni orúkọ inagijẹ òṣèré tí a mọ sí Taiwo Hassan? | |
70460#0 Ile-iwe ko giga ẹwo ni Yvonne Orji ti ka'we? | |
70493#0 Ipo wo ni won fi Kemi Adeosun si labe ijoba Muhammadu Buhari | |
70503#0 Ilu wo ni won bi Agnes Osazuwa si? | |
70557#0 Ede wo ni wọn sọ ni orile-ede Burkina? | |
70571#0 Omo ilu wo ni Mercy Johnson? | |
70576#0 Ipinle wo ni Ibrahim Shekarau ti jẹ gomina? | |
70598#0 ọdún wo ni Ogun àdùbí bẹrẹ? | |
70614#0 Odun wo ni Chioma Ajunwa yege ni idije olympiiki? | |
70629#0 Fiimu meloo ni Ini Ikpe ti ṣe? | |
70633#0 ọdún wo ni akọwe Frances Welsing fi aiyé silẹ? | |
70656#0 Orile ede wo ni Marina Niava to wa? | |
70693#0 Ọdún wo ni Leopold Senghor di ààrẹ orile-ede Senegal? | |
70729#0 Ta ni o se oludari fiimu Mionga ki Obo? | |
70783#0 ọdún wo ni wọn bí Anọbi Muhammad? | |
70918#0 Ki ni orukọ inagije Temilade Openiyi? | |
70933#0 Ẹgbẹ olóṣèlú wo ni Adeniran Ogunsanya bá ṣe? | |
70964#0 Odun wo ni Akiwunmi Ambode jẹ gomina ipinlẹ Eko? | |
70974#0 Ta ni o da ile iṣẹ Mainframe silẹ? | |
70993#0 ipò ìjọba wo ni Femi Adesina wa labẹ ijoba Aare Buhari? | |
70994#0 Orile ede wo lo yege idije World Cup ti 2006? | |
71068#0 Awọn nkan wo ni wọn fi n ṣe Baba Ghanoush? | |
71092#0 Awo wo ni Temi Dee kọkọ gbé jade? | |
71178#0 Ipinle wo ni Ayodele Fayọse ti ṣe gomina? | |
71200#0 Ọdún wo ni Ezra Olubi da ilé iṣẹ Paystack silẹ? | |
71202#0 Iṣẹ wo ni Tiwalola Olanubi n ṣe? | |
71220#0 yunifasiti wo ni denrele ti kàwé? | |
71252#0 ki ni anfani ere idaraya? | |
71280#0 Ta ni ọkọ Naa Ashorkor? | |
71282#0 Ọdún wo ni ọgbẹni Rauf Aregbesola jẹ gomina ipinlẹ Ọsun? | |
71307#0 ọdún wo ni Michael Jackson gbe awo Thriller jáde? | |
71352#0 konsonanti mélòó ló wà nínú èdè Yorùbá? | |
71424#0 Odun wo ni Oluwaseun Osewa da Nairaland silẹ? | |
71511#0 oṣu wo ni odun 1999 ni Olusegun Obasanajo di Aarẹ orile ede Naijiria? | |
71529#0 Odun wo ni Vivica Fox bẹrẹ si ṣe ere itage? | |
71554#0 Odun wo ni Facebook ra Whatsapp? | |
71569#0 Odun wo ni arun coronavirus bẹrẹ? | |
7183#0 orile ede wo ni odo mississipi wa? | |
7208#0 Ọjọ mélòó ló wà nínú oṣù Dìsẹ́mbà? | |
7523#0 Kí ni orúkọ abisọ Kwame Ture? | |
8837#0 ẹgbẹ oloṣelu wo ni Boris Johnson wa pẹlu? | |