text
stringlengths
1
44.6M
Àfikún ọdún ẹ̀wọ̀n kò tó, arábìnrin igbá-kejì Ààrẹ MPLA [Àjọ Àwọn ènìyàn tó fẹ́ ìdásílẹ̀ Angola], Ó nílò kí orílẹ̀-èdè ṣe ìdásílẹ̀ àwọn ìlànà àtilẹ̀wá tí yóò kojú ìpanilára – Àwọn ohun tí wọ́n fara mọ́ ní 2007 nípa àjọsọ ìlànà Maputo ní láti di ṣíṣe.
Dánudúró! Dánudúró! Agbẹjọ́rò aláhọ́n oyin! Má yí mi lọ́kàn padà!
Ǹkan tí a nìlò báyìí ni ọ̀nà-àbáyọ òṣèlú.
Bí bẹ́ẹ̀kọ́, wọn á sọ ibẹ̀ di pápá ogun.
Ní ibi Àpérò Òmìnira Ẹ̀rọ-ayélujára ní Ilẹ̀-Adúláwọ̀ (FIFA) tí ó wáyé ní Accra, Ghana, ikọ̀ akópa láti àwọn ìlú ilẹ̀ Adúláwọ̀ pátá sọ wípé kò ní ṣe ẹnu rere bí ìjọba bá fi òfin de ọmọ-ìlú tí ó ń lo ẹ̀rọ-ayárabíaṣá.
Àwọn akẹ́kọ̀ọ́ láti Iléèwé Orin kíkọ Àwọn Orílẹ̀-èdèe Dhow (DCMA) ń fi qanun, fèrè, ìlù àti dùrù ní Ilé Àwọn Ẹ̀ṣọ́ Aṣọ́bodè Àtijọ́, ní Stone Town, Zanzibar, 2019. DCMA ló ni àwòrán.
Èyí yóò yí ìwé náà padà sí àwòrán tàbí sí HTML, tí yóò dí gbígbé iṣẹ́-àìrídìmú àìdára lọ́wọ́ lórí ẹ̀rọọ̀ rẹ.
Ìpinnu yẹn, yóò gba ìdájọ́ ọmọ ènìyàn, ó dẹ̀ wọ́n.
Obìnrin náà sọ wípé ìwé ìrìnnà nìkan kò gbé ènìyàn wọ orílẹ̀-èdè mìíràn nítorí pé "o ní láti dáhùn àwọn ìbéèrè bíi, ‘Kí ló wa síbí wá ṣe?"
Bí wọn kò bá fẹ́ràn ara wọn, dájú dájú wọ́n gbọ́dọ̀ máa dẹ ara wọn!
“Ipárẹ ti pin láti àkókò yìí lọ”!
Ilé-iṣẹ́ náà pèse èrọ-ìbánisọ̀rọ̀ alágbèká àti iṣẹ́ ẹ̀rọ tó rọjú fún mílíọ́nù ọmọ ilẹ̀ Adúláwọ̀, ní àwọn orílẹ̀-èdè tí wọ́n kúṣẹ̀jùlọ tí wọ́n sì ní ìwà-ìbàjẹ́ jùlọ ní ẹkùn náà -- mò ń sọ nípa orílẹ̀-èdè bi Congo, Malawi, Sierra Leone àti Uganda.
A kì í bínú ààtàn ká dalẹ̀ sígbẹ̀ẹ́.
Ilé ọkọ gidi kún fún ènìyàn àti ìmọ̀lára ènìyàn.
Ṣé àwọn alámọ̀dájú tuntun yìí á mọ̀ dájú dánu?
Àṣé o mọ ìwọ̀n ìṣòro tí ìwọ àti àwọn ènìyàn rẹ ń fún ọmọ mi láti gbé?
Síbẹ̀, àwọn akẹ́kọ̀ọ́ ilé-ẹ̀kọ́ gíga ṣe àròjinlẹ̀.
Àwọn tí ó ń lo ẹ̀rọ-ayárabíaṣá ti ṣe àmúlò ẹ̀rọ-alátagbà láti fi pe ìjọba sí àkíyèsí, bíi ti ìdádúró-lẹ́nu-iṣẹ́ ti CJN, bí bẹ́ẹ̀ kọ́, kò bá ti máà jẹ́ mímọ̀ fún ọmọ ìlú.
Dídókówò nínu ìṣẹ̀da tó máa ń jẹ́ kí àwọn èròjà túbọ̀ rọjú fún ọ̀pọ̀ ènìyàn kò ní kojú ọ̀wọ́n yìí nìkan ṣùgbọ́n yóò pèse ọ̀nà ìpawó wọlé fún àwọn ìjọba láti dawó padà sínú ọrọ̀-ajé láti ró ilé-iṣẹ́ wọn lágbára.
Ó se pàtàkì kí Làbákẹ́ dá a kọjá bí ó bá ti ń wọ yàrá rẹ̀ kí tiẹ̀ lè túbọ̀ bá a ní tọkàn-tarà.
Nítorí náà, Ìrònú náà lọ báyìí: ní àwùjọ tó kúṣẹ̀ tí wọ́n sì ní ìwà-ìbàjẹ́, ìgbìyànjú wa tó dára jù láti mú àdínkù bá ìwà-ìbàjẹ́ ni láti ṣẹ̀dá àwọn ọ̀fin gidi, ká lòwọ́n dáadáa, èyí ó sì ṣínà fún ìdàgbàsókè àti ìṣẹ̀dá ǹkan ọ̀tun láti gbòòrò si.
Ní ọjọ́ 21, àwọn ọlọ́pàá sọ fún àwọn òbíi Deng láti máà gba agbẹjọ́rò fún un.
Ogun tí olójú méjì rí sá ni olójú kan ní òún ń lọ jà.
Àbájáde Ìwádìí Pew ọdún-un 2018 sọ wípé iye àwọn aṣípòkiri láti Ìlú Gúúsù Aṣálẹ̀ Sahara "ti fi ìdá 50 lọ sókè tàbí jù bẹ́ẹ̀ lọ ní àárín-in ọdún-un 2010 àti 2017, ju gbogbo rẹ̀ lọ wọn ju ìdá 17 lọ káríayé ní àsìkò kan náà".
"Wàhálà ni mo sì i ń ri yìí", màmá gbọ́ ti Èṣùníyì sọ èyí “Ìjọ̀ngbọ̀n ó tí ì parí pátápátá.
Màmá, ọmọ yín ò ní kọ̀ láti wá sí abúlé'. Èṣùníyì sọ, Màá tẹ̀lé yín lọ láti mú un wá.
“Gbogbo wá? Tani? Èmi? Ìtìjú? Ṣé ó yẹ kí ojú ti mí nínú ilé Àlàmú?”.
Bàbá Tinú wà lálàáfíà, àbí ṣe yóò sọ pé kò sí lálàáfíà ni?
Ọ̀rọ̀ Ìkórìíra Ẹ̀yà àti Ayédèrú Ìròyìn tàn ká lórí Twitter
O ó ti máa lo 2FA nínú ìgbé ayéè rẹ.
Yunifásitì kan náà ni àwọn méjèèjì si lọ.
O ti jìyà, mo mọ̀ ọ́n.
Awọn Ìkànnì Ilé-ìṣiṣẹ́ Kolibri
Àwọn oníṣẹ́-ìwádìí ti rí i pé ìrọ́ máa ń yára fọ́nká nígbà mẹ́wàá ju àwọn ìtàn tó péye lọ.
Àwọn ìyá máa ń ṣe ìtọ́jú àwọn ọmọ, ṣe ìtọ́jú ilé.
Agbára lórí ìṣàkóso àtẹ̀jáde ìròyìn fẹsẹ̀ múlẹ̀ rìnrìn ní orílẹ̀-èdè China, àti pé, ìwọ̀yáàjà ètò káràkátà pẹ̀lú Orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà, àti bí ọrọ̀-ajé wọn ṣe ń dẹnukọlẹ̀, bí wọ́n bá ṣe yanjú ìṣòro kòkòrò àìfojúrí kòrónà ti Wuhan náà ni yóò forí lé ní ọdún 2020.
Ó yẹ ẹni gbogbo kó sọ pé “Ọlọ́run a-ṣèkan-má-kù,” kò yẹ akúkó.
Bó ṣe sọ fún mi, ó sì ń dàbì ẹni pé ẹgbẹ̀run ojú ló ń wo ìhòhò òun, bó tilẹ̀ jẹ́ wí pé, nínu ọpọ̀lọ, ó mọ̀ wí pé ara òun kọ́.
Ọ̀pọ̀ àwọn orílẹ̀-èdè ní ilẹ̀ Adúláwọ̀ ti ń gbé ìgbésẹ̀ láti ṣe àdínkù ìtànkálẹ̀ kòkòrò àrùn COVID-19.
Ní ìṣẹ́jú kan, ó jáde kúrò nínú yàrá kékeré, ó sì yọjú wo ìyàrá Àlàmú.
Ó sọ síwájú sí i:
Àmọ́ kí ẹnikẹ́ni máà rò wípé iṣẹ́ ọpọlọ nìkan ni ìrìnàjò sí Ìwọ́de Ojúnà.
Àgbà kì í wà lọ́jà kórí ọmọ titun wọ́.
Ó sì máa ri bẹ́ẹ̀, bí ó tilẹ̀ jẹ́ fún ìgbà díẹ̀.
Kó-tán-kó-tán lajá ń lá omi.
“Bẹ́ẹ̀ ni. Bẹ́ẹ̀ ni, Làbákẹ́….ó ti tú – àṣírí.
Kíkúndùn ìṣàkóso ìròyìn ti fún ìjọba lọ́rùn, àti ìjọba ìbílẹ̀ àti ìjọba àpapọ̀ ní àárín gbùngbùn, ló máa ń fa ìdádúró fún àgbéjáde ìròyìn tí yóò ṣe ará ìlú láǹfààní fún ọ̀sẹ̀ pípẹ́.
Wọ́n ti bẹ̀rẹ̀ si í sọ̀rọ̀ pẹ̀lú ìbínú...
Bí o bá ti mú ohun-èlò yìí ṣiṣẹ́ pọ̀ mọ́ Ẹnu-àbáwọlé Ìwífún-alálàyé Kolibri tàbí ṣiṣẹ́ pọ̀ mọ́ ẹ̀rọ mìíràn lórí ìṣàsopọ̀ agbègbè rẹ, ó ṣe é ṣe kí o gbé e padà sí orí ẹ̀rọ yìí.
Àwọn ọ̀dọ́ ní Zanzibar mọ rírìi ìṣẹ̀lẹ̀ àtẹ̀yìnwá tí ó ní ohun ńlá ní í ṣe fún ọjọ́ ọ̀la wọn, ni wọ́n fi ń ṣe àdàlù èyí tí a rí nínú àwọn orin òde òní tí wọn ń gbé jáde.
Ní Tanzania, ìgbéyàwó ọmọdébìnrin kì í jẹ kí ọmọdébìnrin ó kàwé tí wọn kò sì ní àǹfààní láti parí ẹ̀kọ́ọ wọn, gẹ́gẹ́ bí èsì ìwádìí láti Tanzania National Survey, 2017 ṣe ní i lákọsílẹ̀.
A pèsè òògùn aládálù kan tó ní tocilizumab, tí a ń lò lọ́wọ́lọ́wọ́ láti tọ́jú làkúrégbè, àti reparixin, tí à ń lò lọ́wọ́lọ́wọ́ fún ìwádìí ajẹmọ́-ìtọ́jú ààrun jẹjẹrẹ ọyàn.
Ó dáa, ní ọdún 2001, nígbà tí ó jẹ́ wí pé àyẹ̀wò péréte àti hóró òògùn kan ló wà, nọ́ọ́sì kan, lásíkò ìṣẹ́jú péréte rẹ̀ pẹ̀lú aláìsàn kan, ní láti ṣe ìdánilẹ́kọ̀ fún àyẹ̀wo kòkòro apa sójà ara, ṣe àyẹ̀wo kòkòrò apa sójà ara, ṣàlàye èsì, fún wọn ní hóró òògùn kan, Nevirapine, ṣàlàye bí wọn ó ṣe lò ó, jírórò àwọn ẹ̀yan ìfọ́mọlọ́mú, ṣe ìwúrí fún ìfọ́mọlọ́mú, kó sì ṣe àyẹ̀wò fún ìkókó náà – ní ìṣẹ́jú díẹ̀.
Jẹ́ rírí fún àwọn akẹ́kọ̀ọ́ lò
Olórí ni wa, aronújinlẹ̀ ni wa, ọlọ́pọlọ pípé ni wa, onímọ̀ ni wa.
Mo ní kòkòro apa sójà ara.
A gbàgbọ́ pé òótọ́ ni wọ́n, pẹ̀lú ìgbàgbọ́ wí pé bẹ́ẹ̀ ni ẹ lè nígbàgbọ́ nínu ǹkan tí ojú àti etí yín bá ń sọ fún yín.
Ní ọdún mẹ́wàá sẹ́yìn tàbí nnkan bẹ́ẹ̀ ni wọ́n sọ pé ìdíje náà ní màgòmágó nínú — pẹ̀lu ìlọ́wọ́sí àwọn alẹ́nulọ́rọ̀ tí ó ni ilé iṣẹ́ ìgbóhùnsáfẹ́fẹ́, afiorin-tí-a-ti-ká-sílẹ̀ dá àwọn ènìyàn lára dá àti àwọn aláṣẹ ilé iṣẹ́ orin kíkọ tí a mọ̀ sí “jàndùkú soca” — kò ì yọ́ ìgbàgbọ́ wípé Ìwọ́de Ojúnà jẹ́ ohun àwọn ènìyàn.
A ti ṣe àpèjúwe Trump gẹ́gẹ́ bí “ọ̀kan lára àwọn olórí àgbáyé sáà tí a wà yìí tí ó ní ọkàn líle.”
Ní oríi 2019 Henley Passport Index, Japan àti Singapore ni orílẹ̀-èdè tí ó rọrùn fún jù lọ láti ríwèé gbà wọ̀lú oríṣìíríṣi, nígbàtí Angola, Egypt àti Haiti wà ní ìsàlẹ̀.
Kò sí obìnrin náà lórí ilẹ̀ ní gbogbo ayé tí inú rẹ̀ dún tó bí inú rẹ̀ ṣe dùn.
Ìdáhùn rẹ ti fẹ́rẹ̀ẹ́ tọ́, ṣùgbọ́n ó ku <code>\\%</code> kan ní ìparí.
Rántí, ó rọrùn láti ṣe àyédèrú ímeèlì kí ó ba han ojúlé ìdápadà ímeèlì ẹ̀tàn.
Fún àwọn iṣẹ́ tó wọ́pọ̀, o lè wo Ìtẹ̀jáde 2FA Ọlọ́jọ́ Méjìláa wa, tó ṣàpèjúwe bí o ṣe lè f'ààyègba 2FA lóríi Amazon, Ilé-Ìfowópamọ́ America, Dropbox, Facebook, Gmail ati Google, LinkedIn, Outlook.com àti Microsoft, PayPal, Slack, Twitter, àti Yahoo Mail.
Ẹgbẹẹgbẹ̀rún àlejò tí ó ń rọ́ wìtìwìtì wá sí ìlú Stone Town, Zanzibar tí ó kún fún ìṣẹ̀lẹ̀ àtẹ̀yìnwá, ti tẹ̀lé ìró orin Iléèwé Orin kíkọ Àwọn Orílẹ̀-èdèe Dhow (DCMA), ilé ẹ̀kọ́ orin kíkọ tí ó ń ṣe ìgbélárugẹ àti ìpamọ́ àwọn àṣà orin erékùṣù náà tí ó sún mọ́ Swahili ní ẹ̀báa Omi Òkun India.
Ọ̀rẹ́ mi ò ya wèrè.
“Ẹ̀rín ni ó máa ń rín ní gbogbo ìgbà.
Wọ́n tún ṣe bẹ́ẹ̀, wọ́n mú okùn ìkòkò ìse-ìrẹsì.
“Kò sí ǹkankan Màmá, gbogbo wa la wà dáadáa. Làbákẹ́ sẹ̀sẹ̀ jáde pẹ̀lú Tinú. Wọn á tóó dé. A wà dáadáa”.
Nítorí wípé iyùn máa fún ẹja ní oúnjẹ, òun náà ni ó dúró gẹ́gẹ́ bí ilé fún àwọn ẹja àti fún àwọn ọmọ ẹja tí kòì tíì lè wẹ̀ nínú alagbalúgbú omi, nítorí ìdí èyí, bí a bá pàdánùu wọn, ẹja náà yóò bá wọn lọ.
Èyí sì ṣe pàtàkì láti rí ọ̀nà àbáyọ kúrò nínu ìdẹ́yẹsí.
Ó dáa Sènábù, ìyẹn dára, dúró dè é, lọ dúró nínú yàrá rẹ títí ọ̀gá á fi padà dé?
Mo ti ní kòkòro apa sójà ara.
Nítorí náà ǹkan tí àwọn nọ́ọ́sì máa ń ṣe ni wí pé wọn máa ń sọ fún àwọn ìya olùbánidámọ́ràn pé kọ́ ṣàlàye bi wọn yóò ṣe lo òògùn, àti ewu rẹ̀.
Russia wà ní ipò 75 nínú àwọn orílẹ̀-èdè 149 tí Àjọ tó-ń-ṣètò-ọrọ̀-Ajé Lágbàáyé ṣàyẹ̀wò fún lọ́dún 2018 nínú Ìjábọ̀ Àlàfo tó wà láàárín Akọ àti Abo Lágbàáyé, ó ń ṣe dáadáa ní ti ìbádọ́gbà nínú rírí ètò ìlera àti ètò ẹ̀kọ́ lò fún àwọn obìnrin, ṣùgbọ́n wọ́n ń fà sẹ́yìn nínú ètò ìṣòfin láti jà fún ẹ̀tọ́ọ wọn.
Láti sọ ìlú Ìbàdàn, di ìlú tí ó mọ́ jùlọ
Ìṣọdẹ-àjẹ́ jákèjádò India
Ní 31 oṣù Ọpẹ, Igbá-kejì Alákòóso Ìgbìmọ̀ Ìjọba àti Ààrẹ Àjọ-tí-ó-ń-fètò-sí Ìmúdọ́gba Akọ-àtabo ní àwùjọ, Zorana Mihajlović náà sọ̀rọ̀ tako àwọn òṣìṣẹ́ ilé ìtajà Maxi pé “ìwà ìbanilórúkọjẹ́ ni wọ́n hù àti pé wọ́n jẹ̀bi.
Ọ̀kan nínú ìkìlọ̀ náà (ọ̀tún) ń tọ́ka sí òfin "Ìmọ̀ràn" ó sì rọ olùkọ́ àti akẹ́kọ̀ọ́ láti kọ àyájọ́ tí ó fi ara jọ ti Òyìnbó sílẹ̀.
Health Barta gbé fídíò kan sí oríi YouTube tí ó ń ṣe àlàyé lẹ́kùnúnrẹ́rẹ́ ohun tí ó pọn dandan láti ṣe bí èèyán bá ní ibà-ẹ̀fọn:
Làbákẹ́ pariwo, “kí rè é Àlàmú!” Ojú rẹ̀ rí sìgá tí ọkọ rẹ̀ mú sáàárín ìka méjì lọ́wọ́ òsì rẹ̀.
Lójoojúmọ́, lọ́sọ̀ọ̀sẹ̀, a máa ń gba àwọn àdéhùn àti àsọtẹ́lẹ̀.
"Àjọ Oúnjẹ Alẹ́ Olúwa", àwòrán tí a kùn lódà ní 1442 láti ọwọ́ Fra Angelico. Àwòrán tí kò ní olóhun láti orí Wikipedia.
Ẹ wòó, ìgbàkúùgbà tí àwọn ènìyàn bá ti máa rí ànfàní látara ìní ànfàní sí ǹkan tó ṣọ̀wọ́n, èyí máa ń jẹ́ kí ìwà-ìbàjẹ́ wọjú.
Làbákẹ́ ẹni ègún.
Mo lẹ̀rọ pé á bà ọ́ lọkàn jẹ́ ni, Làbákẹ́
Láìpẹ́, ó ti ń dúró lójúkojú pẹ̀lú ẹ, tìrúnú-tìrúnú ni ó fi ń mí.
“Ẹ fà á wọlé” ló yẹ ẹlẹ́ṣin.
Ó gbé apẹ̀rẹ̀ rẹ̀ sílẹ̀ ó sì dúró fún ìgbà díẹ̀, ó ń wo onírùngbọ̀n àti irun orí kíkún tó wà níwájú rẹ̀.
Àwọn ọ̀ràn ìwà ọ̀darànmọràn yìí ti mú ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn obìnrin ní orílẹ̀-èdè Angola dúró gírígírí, èyí sì fa ìpolongo tuntun kan tí ó ń tako ìjìyà abẹ́lé tí wọ́n pe àkóríi rẹ̀ ní "Ẹ Yé é Pa àwọn Obìnrin" tí Ẹgbẹ́ Ondjango tí ó jẹ́ àjọ ajàfúnẹ̀tọ́ obìnrin tí kì í ṣe ti ìjọba ṣe àgbékalẹ̀ẹ rẹ̀.
Ṣe a ó kò tẹ̀síwájú ní ọ̀nà àìṣe é gbáralé àti ìgbàgbọ ohun tí a fẹ́ gbàgbọ́, ká ṣépè fún òtítọ́?
Tayọ̀tayọ̀ ló máa fi tẹ̀lé wa.
COVID-19: Ìpolongo àǹfààní ìrànwọ́ MB ẹgbẹ̀rún 2 láti mú kí àwọn ará ìlú Cape Verde ó jókòó kalé kí òfin kónílégbélé ó bá f'ẹsẹ̀rinlẹ̀.
Àwọn ìyá tí wọ́n ń ran àwọn ìyá lọ́wọ́ láti jagun ààrun kòkòro apa sójà ara.
Àwọn kan tẹ̀lée padà sílé, wọ́n sì ya àwòrán nínú ilée wọn.
Ṣùgbọ́n kò rí bẹ́ẹ̀.
Ẹ ò sì mọ ẹni tí ẹ lè fi ọ̀rọ̀ lọ̀, nítorí ọ̀títọ́ ibẹ̀ ni wí pé, kòkòro apa sójà ara máa ń fa ìdẹ́yẹsí débi wí pé tí olólùfẹ́ẹ̀ rẹ, ẹbíì rẹ, ẹnikẹ́ni nínu iléè rẹ, wọ́n lè lé ẹ síta láìsí àtìlẹyìn Kankan.
Kò bú ramú-ramù mọ́
Ìdáhùn rẹ̀?
Atiku Abubakar