_id
stringlengths
17
21
url
stringlengths
32
377
title
stringlengths
2
120
text
stringlengths
100
2.76k
20231101.yo_2135_3
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%8Cb%C3%A0d%C3%A0n
Ìbàdàn
Àwọn Bírítéénì ṣe àgbékalè ìlú amọ́nà láti ṣe àkóso ètò ọrọ̀ ajé ní agbègbè Ìbàdàn tí ó ṣí gbòrò láìpẹ́ gbòógì ilẹ̀ ètò ọrọ̀ ajé. Ìlú Ìbàdàn ní ó gba àlejò Ilé ẹ̀kọ́ gíga àkọ́kọ́, Yunifásítì ti Ibadan tí wọ́n kọ́kọ́ dá sílẹ̀ gẹ́gẹ́ kọ́lẹ̀jì tí Yunifásítì Lọ́ńdọ̀nì ni ọdún 1948 tí ó padà di Yunifásítì tí ó dá dúró ní ọdún 1962. Ó wà lára àwọn ilé ẹ̀kọ́ àkọ́kọ́ tí wọ́n dá mọ̀ ní orílẹ̀ Áfíríkà. Àwọn ilé ẹ̀kọ́ gíga mìíran tí ó wà ní ìlú Ìbàdàn ní politẹ́kíníkì ìlú Ibadan, Lead City Yunifásítì, àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ. Àwọn ilé ẹ̀kọ́ àkọ́bẹ̀rẹ̀ àti girama náà pọ̀ káàkiri ìlú Ìbàdàn àti agbègbè rẹ̀.
20231101.yo_2135_4
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%8Cb%C3%A0d%C3%A0n
Ìbàdàn
Wọ́n pín Ìbàdàn sí àgbègbè ìjọba Ìbílẹ̀ mọ́kànlá. Márùn-ún wà ní ìgboro Ìbàdàn, mẹ́fà yòókù sì wà ní etílé.
20231101.yo_2136_0
https://yo.wikipedia.org/wiki/T.M.%20Il%C3%A9sanm%C3%AD
T.M. Ilésanmí
Ọ̀jọ̀gbọ́n Thomas Makanjuola Ilésanmí ni ẹni àkọ́kọ́ tí ó gba oyè B. A ní ẹ̀ka-ẹ̀kọ́ èdè àti Lítíréṣọ̀ Áfíríkà ní Yunifásítì Ọbáfẹ́mi Awólọ́wọ̀. Ó jẹ́ Àlùfáà ti ijọ́ Páàdì (ìjọ Kátólíìkì mímọ́). Ó ṣiṣẹ́ ní ẹ̀ka ẹ̀kọ́ yìí láti ọdún 1975 tí ó sì fẹ̀hìntì ní ọdún 2005 .  Ọ̀pọ̀lọpọ̀ iṣẹ́ ni Ọ̀jọ̀gbọ́n yìí  ṣe lórí èdè àti àṣà Yorùbá. Díẹ̀ lára àwọn iṣẹ́ rẹ̀ ni "Iṣẹ́ ìṣẹ̀ǹbáyé, Yorùbá Orature and Literature: A Cultural Analysis, Àwọn nǹkan abàmì ilẹ̀ Yorùbá, Obìnrin:A Cultural Analysis of Yorùbá women, Ọkùnrin làdá obìnrin làgbà, Àdúrà onígbàgbọ̀, Language of African Traditional Religion àti àwọn mìíràn.
20231101.yo_2136_1
https://yo.wikipedia.org/wiki/T.M.%20Il%C3%A9sanm%C3%AD
T.M. Ilésanmí
Ojogbon T. M. Ilésanmí gba iṣẹ́ olùkọ́ ni Yunifásítì ti Ifẹ̀ (Yunifásítì Ọbáfẹ́mi Awólọ́wọ̀ nísinsìnyí ), Ilé-Ifè, Nàìjíríà , gẹgẹ bii Graduate Assistant ní Ẹ̀ka-ẹ̀kọ́ Èdè Áfíríkà àti Lítíréṣọ̀ ní ọjọ́ kẹẹ̀dọ́gbọ̀ oṣù Bélú, Ọdún 1975 lẹ́yìn ìgbà tó ti gboyè méjì láti Yunifásítì Pontifical, ìlú Róòmù àti Yunifásítì ti Ifẹ̀ .
20231101.yo_2136_2
https://yo.wikipedia.org/wiki/T.M.%20Il%C3%A9sanm%C3%AD
T.M. Ilésanmí
Ó gba ìgbéga lẹ́nu ìṣe tó fi dé ipò Ọ̀jọ̀gbọ́n ni Oṣù Òwàrà, ní ọdún 1997. Ipò yìí ni o wà títí tí ó fi fẹ̀hìntì lẹ́nu iṣẹ́ ní ìbámu pẹ̀lú òfin àlàkalẹ̀ lẹ́nu iṣẹ́ ìjọba ní ọdún 2005.
20231101.yo_2136_3
https://yo.wikipedia.org/wiki/T.M.%20Il%C3%A9sanm%C3%AD
T.M. Ilésanmí
Bí a bá wo àkójọpọ̀ àwọn iṣẹ́ Ọ̀jọ̀gbọ́n yìí, a ó rí pé ẹni tí ó fẹ́ràn ìwádìí ṣíṣe lórí àwọn àkóónú nílẹ̀ Yorùbá, àṣà, ìṣe, èdè, lítíréṣọ̀ alohùn àti àwọn nǹkan yòókù tí ó sódo sínú àmù èrò ìjìnlẹ̀ ní àwùjọ Yorùbá. Ó fẹ́ràn láti máa ṣe iṣẹ́ àṣekára, ó sì jẹ́ ẹni tí ó ṣe é fọkàntán. Àràbà ni láwùjọ akadá, ẹ̀ká Yorùbá kò lè gbàgbé iṣẹ́ ribiribi tí ó ti ṣe láti mú ìdàgbàsókè bá àwùjọ wa.
20231101.yo_2136_4
https://yo.wikipedia.org/wiki/T.M.%20Il%C3%A9sanm%C3%AD
T.M. Ilésanmí
Onimọ̀ tó gbòòrò ni Ọ̀jọ̀gbọ́n Ilésanmí torí pé àwọn iṣẹ́ ìwádìí lórí àwọn ayẹyẹ ìrúbọ àti ìtàn Ìbílẹ̀ múnádóko, wọ́n sì wúlò púpọ̀ fún àwọn akẹ́kọ̀ọ́ èdè Yorùbá fún iṣẹ́ ìwádìí. Ó máa n kó àwọn èèyàn mọ́ra, oníwà ìrẹ̀lẹ̀ sì ni.
20231101.yo_2136_5
https://yo.wikipedia.org/wiki/T.M.%20Il%C3%A9sanm%C3%AD
T.M. Ilésanmí
Láàárín àwọn akẹgbẹ́ rẹ̀, Ọ̀jọ̀gbọ́n Ilésanmí ti bójútó ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn akẹ́kọ̀ọ́ lórí iṣẹ́ àpilẹ̀kọ fún àsekàgbá láti gboyè ní ọ̀kan-ò-jọ̀kan ipele ìkẹ́kọ̀ọ́-gboyè.
20231101.yo_2136_6
https://yo.wikipedia.org/wiki/T.M.%20Il%C3%A9sanm%C3%AD
T.M. Ilésanmí
Onimọ̀ tó làmìlaka ni Ọ̀jọ̀gbọ́n Ilésanmí, ó mú ìmúgbòòrò bá èdè àti àṣà Yorùbá. Ó jẹ́ ìpè Ọlọ́run ní ọjọ́ kẹtàdínlọ́gbọ̀n, Oṣù Èbìbí, Ọdún 2016.
20231101.yo_2162_0
https://yo.wikipedia.org/wiki/%E1%BA%B8%CC%80y%C3%A0%20ara
Ẹ̀yà ara
Òde Ara (Outer Part): Irun (hair), orí (head), iwájú ori(forehead), ojú (eye/face), imú (nose), àgbọ̀n (chin), ẹnu (mouth), orùn (neck), èjìká (shoulder), àyà (chest), ọmú/ọyàn (breast), apá (arm), ikùn (belly), Ìdodo (navel), ọmọ ìka/ika ọwọ́ (fingers), èékánná (finger nail), ìdí (buttock), itan (thigh), ẹsẹ̀ (leg), orókún (knee), ojúgun (shin), ìka ẹsẹ̀ (toes), àtẹ́lẹsẹ̀ (sole of the foot), and gìgísẹ̀ (heel).
20231101.yo_2162_1
https://yo.wikipedia.org/wiki/%E1%BA%B8%CC%80y%C3%A0%20ara
Ẹ̀yà ara
Inú Ara (Inner Part): eyín (teeth), ahọ́n (tongue), ọ̀fun (throat), ọkàn (heart), ẹ̀dọ̀ fóró (lung) ẹ̀dọ̀ki (liver), ẹjẹ̀ (blood) and eran ara (muscle).
20231101.yo_2163_0
https://yo.wikipedia.org/wiki/Or%C3%BAk%E1%BB%8D%20%C3%80d%C3%BAgb%C3%B2%20n%C3%AD%20%C3%92nd%C3%B3%2C%20%C3%8Cp%C3%ADnl%E1%BA%B9%CC%80%20%C3%92nd%C3%B3%2C%20N%C3%A0%C3%ACj%C3%ADr%C3%AD%C3%A0
Orúkọ Àdúgbò ní Òndó, Ìpínlẹ̀ Òndó, Nàìjíríà
Ìtumọ̀: Ibi ti àwọn òyìnbó tó mú èsìn ìgbàgḅó wá, ilé ibi tí wón ń gbé tí ó wà lórú òkè tú wọ́n ń pè ni yádì ni àwọn so di òke àyàdí tí àdúgbò náà ń jé dòní.
20231101.yo_2163_1
https://yo.wikipedia.org/wiki/Or%C3%BAk%E1%BB%8D%20%C3%80d%C3%BAgb%C3%B2%20n%C3%AD%20%C3%92nd%C3%B3%2C%20%C3%8Cp%C3%ADnl%E1%BA%B9%CC%80%20%C3%92nd%C3%B3%2C%20N%C3%A0%C3%ACj%C3%ADr%C3%AD%C3%A0
Orúkọ Àdúgbò ní Òndó, Ìpínlẹ̀ Òndó, Nàìjíríà
Ìtumọ̀: Òrìsà kan tí wọ́n ń pè ní odòlúà ní ó tè àdúgbò yí dò, Ibìtí o wọlẹ̀ si ni à ń pè ni odòlúà.
20231101.yo_2163_2
https://yo.wikipedia.org/wiki/Or%C3%BAk%E1%BB%8D%20%C3%80d%C3%BAgb%C3%B2%20n%C3%AD%20%C3%92nd%C3%B3%2C%20%C3%8Cp%C3%ADnl%E1%BA%B9%CC%80%20%C3%92nd%C3%B3%2C%20N%C3%A0%C3%ACj%C3%ADr%C3%AD%C3%A0
Orúkọ Àdúgbò ní Òndó, Ìpínlẹ̀ Òndó, Nàìjíríà
Ìtumọ̀: Òkè ibi ti ó kọ́lé sí tí ó ń gbé ti peka sí tí wọ́n ń pè ni íÒkèlísà. Lísà ni o wa ní àdúgbò ti a ń pè ni Òkèlísà.
20231101.yo_2163_3
https://yo.wikipedia.org/wiki/Or%C3%BAk%E1%BB%8D%20%C3%80d%C3%BAgb%C3%B2%20n%C3%AD%20%C3%92nd%C3%B3%2C%20%C3%8Cp%C3%ADnl%E1%BA%B9%CC%80%20%C3%92nd%C3%B3%2C%20N%C3%A0%C3%ACj%C3%ADr%C3%AD%C3%A0
Orúkọ Àdúgbò ní Òndó, Ìpínlẹ̀ Òndó, Nàìjíríà
Ìtumọ̀: Igi kan wa ti wọ́n ń pè ní igi sin. Abẹ́ igi yíì fẹjú, ó tutu, ó sì gbòòrò tó bẹ́ẹ̀ tí o lè gba èèyàn púpọ̀ láti seré bíì ìjàkadì ayò ọpọ́n abbl. Béì tití ni àwọn èèyàn bẹ̀rẹ̀ sí kọ́lé sí àyíká igi yi ti ó wá di ibi tí à ń pè ni idi isin di òní.
20231101.yo_2163_4
https://yo.wikipedia.org/wiki/Or%C3%BAk%E1%BB%8D%20%C3%80d%C3%BAgb%C3%B2%20n%C3%AD%20%C3%92nd%C3%B3%2C%20%C3%8Cp%C3%ADnl%E1%BA%B9%CC%80%20%C3%92nd%C3%B3%2C%20N%C3%A0%C3%ACj%C3%ADr%C3%AD%C3%A0
Orúkọ Àdúgbò ní Òndó, Ìpínlẹ̀ Òndó, Nàìjíríà
Ìtumọ̀: ni àdúgbò ti àwọn onísòwò tí ó jẹ́ ìsòbò pọ̀ si wọn a sì máa se kárà kátà wọn ní àdúgbò náà idi nìyí tí Òndó ń fi ń pe àdúgbò náà ni Òkè ìsòwò ni wọ́n igbati ó jẹ́ wí pé òkè ni ó wà. Òkè ìsòwò yíì ni àwọn ìsòbò yíì se àsìse ni pípé rè tí wọ́n fi ń pè ní òkè ìròwò ti ó di òkèrówó títí di òní.
20231101.yo_2163_5
https://yo.wikipedia.org/wiki/Or%C3%BAk%E1%BB%8D%20%C3%80d%C3%BAgb%C3%B2%20n%C3%AD%20%C3%92nd%C3%B3%2C%20%C3%8Cp%C3%ADnl%E1%BA%B9%CC%80%20%C3%92nd%C3%B3%2C%20N%C3%A0%C3%ACj%C3%ADr%C3%AD%C3%A0
Orúkọ Àdúgbò ní Òndó, Ìpínlẹ̀ Òndó, Nàìjíríà
Ìtumọ̀:Ó jẹ́ ibi ti Ògbóni ti bẹ̀rẹ̀ ti wọn n ko ìlédi wọn si, ti wọn bà si ń lọ wọn a mú Ogbó dani gẹ́gẹ́ bí àmìn ẹgbẹ́ wọn. Wọn á ma so wí pé à kìí wòó Àdúgbò yí ni wọn sọ di Ogbo-ti-a-kii-wò tì ò fi di Ògbònkowo lónìí
20231101.yo_2163_6
https://yo.wikipedia.org/wiki/Or%C3%BAk%E1%BB%8D%20%C3%80d%C3%BAgb%C3%B2%20n%C3%AD%20%C3%92nd%C3%B3%2C%20%C3%8Cp%C3%ADnl%E1%BA%B9%CC%80%20%C3%92nd%C3%B3%2C%20N%C3%A0%C3%ACj%C3%ADr%C3%AD%C3%A0
Orúkọ Àdúgbò ní Òndó, Ìpínlẹ̀ Òndó, Nàìjíríà
Ìtumọ̀: Ọjọ́ ti Òndó ìbá dàrú tí Òndó ìbá túká nítorí awo nlá kan to sẹlẹ̀, ojú ibi tí wọn joko si pètù sọ́rọ̀ òhún.
20231101.yo_2163_7
https://yo.wikipedia.org/wiki/Or%C3%BAk%E1%BB%8D%20%C3%80d%C3%BAgb%C3%B2%20n%C3%AD%20%C3%92nd%C3%B3%2C%20%C3%8Cp%C3%ADnl%E1%BA%B9%CC%80%20%C3%92nd%C3%B3%2C%20N%C3%A0%C3%ACj%C3%ADr%C3%AD%C3%A0
Orúkọ Àdúgbò ní Òndó, Ìpínlẹ̀ Òndó, Nàìjíríà
Ìtumọ̀: ìdí tí wọ́n fi ń pè wọ́n ni ọ̀kà ni pé àwọn ará Ọ̀kà Àkókó lo fi agbègbè yí se ibùgbé. Àwọn ará òkà yii si ti pẹ̀ ni Òndó to bee je ti won ti gbo èdè Òndó yinrinyirin se téwé bá pe lára ose a dose ìdí nì yen tí won ń fi pé won ní òkà Ondo ti o doruko àdúgbò won ti a mo si oka
20231101.yo_2163_8
https://yo.wikipedia.org/wiki/Or%C3%BAk%E1%BB%8D%20%C3%80d%C3%BAgb%C3%B2%20n%C3%AD%20%C3%92nd%C3%B3%2C%20%C3%8Cp%C3%ADnl%E1%BA%B9%CC%80%20%C3%92nd%C3%B3%2C%20N%C3%A0%C3%ACj%C3%ADr%C3%AD%C3%A0
Orúkọ Àdúgbò ní Òndó, Ìpínlẹ̀ Òndó, Nàìjíríà
Ìtumọ̀: Ijoye nla kan lo nje yege, ibi to tedo di to n gbe bo si owo isale Òndó ìdí niyi ti won fi n pe won ni òdò yègè.
20231101.yo_2163_9
https://yo.wikipedia.org/wiki/Or%C3%BAk%E1%BB%8D%20%C3%80d%C3%BAgb%C3%B2%20n%C3%AD%20%C3%92nd%C3%B3%2C%20%C3%8Cp%C3%ADnl%E1%BA%B9%CC%80%20%C3%92nd%C3%B3%2C%20N%C3%A0%C3%ACj%C3%ADr%C3%AD%C3%A0
Orúkọ Àdúgbò ní Òndó, Ìpínlẹ̀ Òndó, Nàìjíríà
Ìtumọ̀: Ojà ni won n pen i igele ni èdè Òndó. Tomodé tàgbà won ni o ma fi aro wọn lo oko ni agbèègbè ti a n soro bayii nigba ti o ba di owo, ale won a pate oja won si ita ile won, titi ti o fid i ojà ti won náà ni alale.
20231101.yo_2163_10
https://yo.wikipedia.org/wiki/Or%C3%BAk%E1%BB%8D%20%C3%80d%C3%BAgb%C3%B2%20n%C3%AD%20%C3%92nd%C3%B3%2C%20%C3%8Cp%C3%ADnl%E1%BA%B9%CC%80%20%C3%92nd%C3%B3%2C%20N%C3%A0%C3%ACj%C3%ADr%C3%AD%C3%A0
Orúkọ Àdúgbò ní Òndó, Ìpínlẹ̀ Òndó, Nàìjíríà
Ìtumọ̀: Ó jé agbègbè ti okuta pos i agbegbe yin i àwon molé molé ti n ma wa ko okuta àwon ni o si so agbegbe naa di ibi-a-n-gbo-òkútà oun lo wa di ìgbònkúta lóní
20231101.yo_2163_11
https://yo.wikipedia.org/wiki/Or%C3%BAk%E1%BB%8D%20%C3%80d%C3%BAgb%C3%B2%20n%C3%AD%20%C3%92nd%C3%B3%2C%20%C3%8Cp%C3%ADnl%E1%BA%B9%CC%80%20%C3%92nd%C3%B3%2C%20N%C3%A0%C3%ACj%C3%ADr%C3%AD%C3%A0
Orúkọ Àdúgbò ní Òndó, Ìpínlẹ̀ Òndó, Nàìjíríà
Ìtumọ̀: lósìnlá-là gbalá ni àpètán lósùlá ibè ni won ti kókó ń se osùn tí won ńrà osìn, tí won ńtà osìn ní Ondo.
20231101.yo_2163_12
https://yo.wikipedia.org/wiki/Or%C3%BAk%E1%BB%8D%20%C3%80d%C3%BAgb%C3%B2%20n%C3%AD%20%C3%92nd%C3%B3%2C%20%C3%8Cp%C3%ADnl%E1%BA%B9%CC%80%20%C3%92nd%C3%B3%2C%20N%C3%A0%C3%ACj%C3%ADr%C3%AD%C3%A0
Orúkọ Àdúgbò ní Òndó, Ìpínlẹ̀ Òndó, Nàìjíríà
Ìtumọ̀: àwon òlàjú ti o kókó lo sí Èkó ti won tàjò dé ni won so agbegbe yin i sùrúlérè nigba ti won tàjò de lati ma fí rántí agbègbè tí won gbé ni Èkó
20231101.yo_2163_13
https://yo.wikipedia.org/wiki/Or%C3%BAk%E1%BB%8D%20%C3%80d%C3%BAgb%C3%B2%20n%C3%AD%20%C3%92nd%C3%B3%2C%20%C3%8Cp%C3%ADnl%E1%BA%B9%CC%80%20%C3%92nd%C3%B3%2C%20N%C3%A0%C3%ACj%C3%ADr%C3%AD%C3%A0
Orúkọ Àdúgbò ní Òndó, Ìpínlẹ̀ Òndó, Nàìjíríà
Ìtumọ̀: Àwon òlàjú ti o koko lo sí Èkó ti won tajo dé ni won so agbègbè yin í Yaba nígbà tí won tàjò dé láti le ma fi rántí àgbègbè ti won gbé ní Èkó.
20231101.yo_2163_14
https://yo.wikipedia.org/wiki/Or%C3%BAk%E1%BB%8D%20%C3%80d%C3%BAgb%C3%B2%20n%C3%AD%20%C3%92nd%C3%B3%2C%20%C3%8Cp%C3%ADnl%E1%BA%B9%CC%80%20%C3%92nd%C3%B3%2C%20N%C3%A0%C3%ACj%C3%ADr%C3%AD%C3%A0
Orúkọ Àdúgbò ní Òndó, Ìpínlẹ̀ Òndó, Nàìjíríà
Ìtumọ̀:Jé ìtà oba tí won ti ń ma pa olè àti òdaràn idà ni a fi ń pa won ibi tí a n tójú idà náà sí ni Ìsídà níwòn ìgbà tí ó si jé pé apá ìsàlè Ondo ló bó sí ni a fi ń pè ní Odòsíndà.
20231101.yo_2163_15
https://yo.wikipedia.org/wiki/Or%C3%BAk%E1%BB%8D%20%C3%80d%C3%BAgb%C3%B2%20n%C3%AD%20%C3%92nd%C3%B3%2C%20%C3%8Cp%C3%ADnl%E1%BA%B9%CC%80%20%C3%92nd%C3%B3%2C%20N%C3%A0%C3%ACj%C3%ADr%C3%AD%C3%A0
Orúkọ Àdúgbò ní Òndó, Ìpínlẹ̀ Òndó, Nàìjíríà
Ìtumọ̀:Ibi tí àwon ará Ondó tí máa ń jo ibi tí ó téjú tí ó gba èrò púpò ni, ó sì bó sí àrín ìlú a sì ma ń se ìpàdé níbè náà pèlú agbègbè yíì ni won ń pè ní òde Ondó.
20231101.yo_2163_16
https://yo.wikipedia.org/wiki/Or%C3%BAk%E1%BB%8D%20%C3%80d%C3%BAgb%C3%B2%20n%C3%AD%20%C3%92nd%C3%B3%2C%20%C3%8Cp%C3%ADnl%E1%BA%B9%CC%80%20%C3%92nd%C3%B3%2C%20N%C3%A0%C3%ACj%C3%ADr%C3%AD%C3%A0
Orúkọ Àdúgbò ní Òndó, Ìpínlẹ̀ Òndó, Nàìjíríà
Ìtumọ̀:Ibè ní agbèbbè tí a ma ńkò àwon omobìnrin tí kò tí mo Okunrin si fun Idabobo lowo isekuse ki won tó ní oko ní ayé àtijó agbègbè náà sì ni eré obìtun ti bèrè.
20231101.yo_2163_17
https://yo.wikipedia.org/wiki/Or%C3%BAk%E1%BB%8D%20%C3%80d%C3%BAgb%C3%B2%20n%C3%AD%20%C3%92nd%C3%B3%2C%20%C3%8Cp%C3%ADnl%E1%BA%B9%CC%80%20%C3%92nd%C3%B3%2C%20N%C3%A0%C3%ACj%C3%ADr%C3%AD%C3%A0
Orúkọ Àdúgbò ní Òndó, Ìpínlẹ̀ Òndó, Nàìjíríà
Ìtumọ̀: O je agbègbè tí òkà ti ń pò ti àwon èèyàn ń rà tí won si ń tà. Ìdí nìyí ti won fi ń pè ní ibi-ìje-okà ti ó di ìjòkà lónìí.
20231101.yo_2163_18
https://yo.wikipedia.org/wiki/Or%C3%BAk%E1%BB%8D%20%C3%80d%C3%BAgb%C3%B2%20n%C3%AD%20%C3%92nd%C3%B3%2C%20%C3%8Cp%C3%ADnl%E1%BA%B9%CC%80%20%C3%92nd%C3%B3%2C%20N%C3%A0%C3%ACj%C3%ADr%C3%AD%C3%A0
Orúkọ Àdúgbò ní Òndó, Ìpínlẹ̀ Òndó, Nàìjíríà
Ìtumọ̀: O je àdúgbò ti èèyàn kan tédó ni pe bayìí ti o so àdúgbò náà ni orúko Tèmídire: Tèmi-di-ire.
20231101.yo_2163_19
https://yo.wikipedia.org/wiki/Or%C3%BAk%E1%BB%8D%20%C3%80d%C3%BAgb%C3%B2%20n%C3%AD%20%C3%92nd%C3%B3%2C%20%C3%8Cp%C3%ADnl%E1%BA%B9%CC%80%20%C3%92nd%C3%B3%2C%20N%C3%A0%C3%ACj%C3%ADr%C3%AD%C3%A0
Orúkọ Àdúgbò ní Òndó, Ìpínlẹ̀ Òndó, Nàìjíríà
Ìtumọ̀: Ó jé agbègbè tí babaláwo kan tí ó gbójú wa ni àtijó a sì máagbà èmí eniyan la pupo lowo iku. Igbàgbó sì ni wipe eni ti o bat i mikanlè lówó Iku lódò rè ko le rí ajínde mo idi niyi ti won fi ń pè ni odò-ìmí-kanlè tí àgékúrú rè wa di odòmíkàn.
20231101.yo_2163_20
https://yo.wikipedia.org/wiki/Or%C3%BAk%E1%BB%8D%20%C3%80d%C3%BAgb%C3%B2%20n%C3%AD%20%C3%92nd%C3%B3%2C%20%C3%8Cp%C3%ADnl%E1%BA%B9%CC%80%20%C3%92nd%C3%B3%2C%20N%C3%A0%C3%ACj%C3%ADr%C3%AD%C3%A0
Orúkọ Àdúgbò ní Òndó, Ìpínlẹ̀ Òndó, Nàìjíríà
Ìtumọ̀: Eni tó ní ilé ni a ń pè ni ‘nuli’ ni èdè Òndó. Agbègbè yi si wa je agbègbè ti àwon oní ilé ń gbé idi niyi ti won fi n pe ni odò-núlí ti ó wá di odòlÍlí
20231101.yo_2163_21
https://yo.wikipedia.org/wiki/Or%C3%BAk%E1%BB%8D%20%C3%80d%C3%BAgb%C3%B2%20n%C3%AD%20%C3%92nd%C3%B3%2C%20%C3%8Cp%C3%ADnl%E1%BA%B9%CC%80%20%C3%92nd%C3%B3%2C%20N%C3%A0%C3%ACj%C3%ADr%C3%AD%C3%A0
Orúkọ Àdúgbò ní Òndó, Ìpínlẹ̀ Òndó, Nàìjíríà
Ìtumọ̀: Orúko ìlagije akíkanjú kan ló ń jé béè. Agbègbè tí ó n gbe ni a fi orúko re so lati se aponle fún un.
20231101.yo_2163_22
https://yo.wikipedia.org/wiki/Or%C3%BAk%E1%BB%8D%20%C3%80d%C3%BAgb%C3%B2%20n%C3%AD%20%C3%92nd%C3%B3%2C%20%C3%8Cp%C3%ADnl%E1%BA%B9%CC%80%20%C3%92nd%C3%B3%2C%20N%C3%A0%C3%ACj%C3%ADr%C3%AD%C3%A0
Orúkọ Àdúgbò ní Òndó, Ìpínlẹ̀ Òndó, Nàìjíríà
Ìtumọ̀: Àgbègbè tí àwon elésìn Kiriyó ti máa se ìsìn won fún ìgbalà okàn ni won pè ní òkè-ìgbàlà ti o wa di okegbala lónìí yíì.
20231101.yo_2164_0
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%88k%C3%B3%2C%20%C3%8Cp%C3%ADnl%E1%BA%B9%CC%80%20%C3%88k%C3%B3%2C%20N%C3%A0%C3%ACj%C3%ADr%C3%AD%C3%A0
Àdúgbò Èkó, Ìpínlẹ̀ Èkó, Nàìjíríà
Ìtumò: Agbègbè yí jé ibi tí àwon ará ìlú orísirísi latí orílè èdè káàkiri gbé ní gbà a ayeye yí ní 1977 (Festival of Arts and culture).
20231101.yo_2164_1
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%88k%C3%B3%2C%20%C3%8Cp%C3%ADnl%E1%BA%B9%CC%80%20%C3%88k%C3%B3%2C%20N%C3%A0%C3%ACj%C3%ADr%C3%AD%C3%A0
Àdúgbò Èkó, Ìpínlẹ̀ Èkó, Nàìjíríà
Ìtumò: Abúlé –Ìjèsà ni apá ibi tí àwon ìjèsà kókó pò sí ní èkó, èyí ni ìdí tí ó fi ńjé Abúlé-Ìjàshà.
20231101.yo_2164_2
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%88k%C3%B3%2C%20%C3%8Cp%C3%ADnl%E1%BA%B9%CC%80%20%C3%88k%C3%B3%2C%20N%C3%A0%C3%ACj%C3%ADr%C3%AD%C3%A0
Àdúgbò Èkó, Ìpínlẹ̀ Èkó, Nàìjíríà
Ìtumò: Ibí ni ówà nínú Èkó, orúko yí ni orúko Oba Èkó níìgbà tó tipé, sùgbó orúko rè ni wón fi so agbègbè yí tí ó ńjé kòsókó road.
20231101.yo_2164_3
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%88k%C3%B3%2C%20%C3%8Cp%C3%ADnl%E1%BA%B9%CC%80%20%C3%88k%C3%B3%2C%20N%C3%A0%C3%ACj%C3%ADr%C3%AD%C3%A0
Àdúgbò Èkó, Ìpínlẹ̀ Èkó, Nàìjíríà
Ìtumò: Orúko ènìyàn Tàfá Bàléwà, eni náà jé lára àwon tí ó ti jé ààre orílè wa, lé yìn ikú rè ni wón fi so ibè ní Tàfá Bàléwà “Square”.
20231101.yo_2164_4
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%88k%C3%B3%2C%20%C3%8Cp%C3%ADnl%E1%BA%B9%CC%80%20%C3%88k%C3%B3%2C%20N%C3%A0%C3%ACj%C3%ADr%C3%AD%C3%A0
Àdúgbò Èkó, Ìpínlẹ̀ Èkó, Nàìjíríà
Ìtumò: Technology Road, ìdí tí wón fi só ní oruko yi nípé, Yaba Technology kò jìnà sí ibè rárá, ìdí náà ni wón fi soóní Technology Road.
20231101.yo_2164_5
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%88k%C3%B3%2C%20%C3%8Cp%C3%ADnl%E1%BA%B9%CC%80%20%C3%88k%C3%B3%2C%20N%C3%A0%C3%ACj%C3%ADr%C3%AD%C3%A0
Àdúgbò Èkó, Ìpínlẹ̀ Èkó, Nàìjíríà
Ìtumò: Ní agbègbè yí enìkan péré ni óní kéké sùgbón nítorí èyí ni won fi so ibè ní kèké, sùgbón ní ìgbà tí àwon òyìnbó fid é ní wón só di kéké.
20231101.yo_2164_6
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%88k%C3%B3%2C%20%C3%8Cp%C3%ADnl%E1%BA%B9%CC%80%20%C3%88k%C3%B3%2C%20N%C3%A0%C3%ACj%C3%ADr%C3%AD%C3%A0
Àdúgbò Èkó, Ìpínlẹ̀ Èkó, Nàìjíríà
Ìtumò: Orúko èyàn ni óún jé Herbert macanlay, eni yì jé okan lára àwon òyìbó tí wón wá sí orílè èdè yí, nítorí èyí ni wón fi só ní Herbert macaulay way.
20231101.yo_2164_7
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%88k%C3%B3%2C%20%C3%8Cp%C3%ADnl%E1%BA%B9%CC%80%20%C3%88k%C3%B3%2C%20N%C3%A0%C3%ACj%C3%ADr%C3%AD%C3%A0
Àdúgbò Èkó, Ìpínlẹ̀ Èkó, Nàìjíríà
Ìtumò: Ní ìlú Èkó ìdí tí wón fi só ní Maryland nipé, orúko aya oba ìlú òyinbó ni Mary, ìdí èyí ni a fi só ní Maryland.
20231101.yo_2164_8
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%88k%C3%B3%2C%20%C3%8Cp%C3%ADnl%E1%BA%B9%CC%80%20%C3%88k%C3%B3%2C%20N%C3%A0%C3%ACj%C3%ADr%C3%AD%C3%A0
Àdúgbò Èkó, Ìpínlẹ̀ Èkó, Nàìjíríà
Ìtumò: Èdè yí ni èdè àwon haúsá, ìtumò rè sì ni kíá-kíá, àwon Haúsá ni wón pò sí ibí yìí jù, ní-ìgbà tí wón tèdó tí bè wón kò mò bí wón áse bá àwon èèyàn sòrò, sùgbón nínú ìwònba ìgbà tí wón ń tajà èdè won ni másámásá, ìdí ètí ni wón fi só ní másámásá-kíá-kíá.
20231101.yo_2164_9
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%88k%C3%B3%2C%20%C3%8Cp%C3%ADnl%E1%BA%B9%CC%80%20%C3%88k%C3%B3%2C%20N%C3%A0%C3%ACj%C3%ADr%C3%AD%C3%A0
Àdúgbò Èkó, Ìpínlẹ̀ Èkó, Nàìjíríà
Ìtumò: Ìdí tí wón fi só ní “coconut village” niípé omi pò ní ibè gan, àti cocoanut (àgbon). O wa ni agbègbè Ajégúnlè.
20231101.yo_2164_10
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%88k%C3%B3%2C%20%C3%8Cp%C3%ADnl%E1%BA%B9%CC%80%20%C3%88k%C3%B3%2C%20N%C3%A0%C3%ACj%C3%ADr%C3%AD%C3%A0
Àdúgbò Èkó, Ìpínlẹ̀ Èkó, Nàìjíríà
Ìtumò: Ajégúnlè jé ibi tí wón ti ń ra jà àti ta jà ní Èkó, àti wípé ibè jé lára ibi tìí àwon èèyàn pòsí ní ìlú Èkó, ojà títà sì ń lo déédéé tí aje ati owó dè tińwolé nígbà náà, ìdí náà ni ófinjé Ajégúnlè.
20231101.yo_2164_11
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%88k%C3%B3%2C%20%C3%8Cp%C3%ADnl%E1%BA%B9%CC%80%20%C3%88k%C3%B3%2C%20N%C3%A0%C3%ACj%C3%ADr%C3%AD%C3%A0
Àdúgbò Èkó, Ìpínlẹ̀ Èkó, Nàìjíríà
Ìtumò: Èyí jé orúko agbègbè kan ní ìlú Agége cinema ńlá kan ní ó wà ní ibè, tí wón pè ní PEN-CINEMA.
20231101.yo_2164_12
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%88k%C3%B3%2C%20%C3%8Cp%C3%ADnl%E1%BA%B9%CC%80%20%C3%88k%C3%B3%2C%20N%C3%A0%C3%ACj%C3%ADr%C3%AD%C3%A0
Àdúgbò Èkó, Ìpínlẹ̀ Èkó, Nàìjíríà
Ìtumò: Ibí ni won sin àwon Ológun tí wón ti won ti kú, wón sìn o àre ńlá kan sí bè tí ó je sójà ológun.
20231101.yo_2164_13
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%88k%C3%B3%2C%20%C3%8Cp%C3%ADnl%E1%BA%B9%CC%80%20%C3%88k%C3%B3%2C%20N%C3%A0%C3%ACj%C3%ADr%C3%AD%C3%A0
Àdúgbò Èkó, Ìpínlẹ̀ Èkó, Nàìjíríà
Ìtumò: Ilú yíì wà ní agbègbè Àpápá ní Èkó, ìlú ńkí jé ibi tí àwon èèyàn pò si, tí àwon sì gbèrò sí gan.
20231101.yo_2164_14
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%88k%C3%B3%2C%20%C3%8Cp%C3%ADnl%E1%BA%B9%CC%80%20%C3%88k%C3%B3%2C%20N%C3%A0%C3%ACj%C3%ADr%C3%AD%C3%A0
Àdúgbò Èkó, Ìpínlẹ̀ Èkó, Nàìjíríà
Ìtumò: Ibì jé agbègbè tí àwon custom pò sí, ibè sì ni ibi tí àwon erù sì pò sí àti àwon kòntánà idí èyí ni wón fi pèéní Tincay-Island.
20231101.yo_2164_15
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%88k%C3%B3%2C%20%C3%8Cp%C3%ADnl%E1%BA%B9%CC%80%20%C3%88k%C3%B3%2C%20N%C3%A0%C3%ACj%C3%ADr%C3%AD%C3%A0
Àdúgbò Èkó, Ìpínlẹ̀ Èkó, Nàìjíríà
Ìtumò: Agbègbè yí ni ówà ní Dòpèmú ní ìlú Èkó, ibè ni àwon ohun ìkólé yìí pò sí (aluminum) ìdí náà ni wón fi ń pèé ní aluminum
20231101.yo_2164_16
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%88k%C3%B3%2C%20%C3%8Cp%C3%ADnl%E1%BA%B9%CC%80%20%C3%88k%C3%B3%2C%20N%C3%A0%C3%ACj%C3%ADr%C3%AD%C3%A0
Àdúgbò Èkó, Ìpínlẹ̀ Èkó, Nàìjíríà
Ìtumò: Agbègbè yí ni wón ti má n já erù tí óún bò láti òkè-ògun àti èyí tí wón bá fé gbé jáde, ìdí èyí ni a fi ń pèé ní “port’
20231101.yo_2164_17
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%88k%C3%B3%2C%20%C3%8Cp%C3%ADnl%E1%BA%B9%CC%80%20%C3%88k%C3%B3%2C%20N%C3%A0%C3%ACj%C3%ADr%C3%AD%C3%A0
Àdúgbò Èkó, Ìpínlẹ̀ Èkó, Nàìjíríà
Ìtumò: Abúlé òsun jé lára ibi tí àwon abò-òrìsà òsun pó sí ní ìlú Èkó èyí ni wón fi só ní Abúlé-òsu, àti pé omí pò ní bè lópòlópò.
20231101.yo_2164_18
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%88k%C3%B3%2C%20%C3%8Cp%C3%ADnl%E1%BA%B9%CC%80%20%C3%88k%C3%B3%2C%20N%C3%A0%C3%ACj%C3%ADr%C3%AD%C3%A0
Àdúgbò Èkó, Ìpínlẹ̀ Èkó, Nàìjíríà
Ìtumò: Kiríkirì ni ibi tí àwon eléwòn má n gbéé kiríkirì sì jé lára, ilé èwèn tí ó tóbí jù, nítorí è ni wón fi ń péè agbègbè náà ní kiríkirì.
20231101.yo_2164_19
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%88k%C3%B3%2C%20%C3%8Cp%C3%ADnl%E1%BA%B9%CC%80%20%C3%88k%C3%B3%2C%20N%C3%A0%C3%ACj%C3%ADr%C3%AD%C3%A0
Àdúgbò Èkó, Ìpínlẹ̀ Èkó, Nàìjíríà
Ìtumò: Abílé-Àdó jé lara ibi ti awon àlàdó pos i ni aiye atijo ni ilu Eko opolopo ni ko mo ibe nitori ise ti won nse ni ibe.
20231101.yo_2164_20
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%88k%C3%B3%2C%20%C3%8Cp%C3%ADnl%E1%BA%B9%CC%80%20%C3%88k%C3%B3%2C%20N%C3%A0%C3%ACj%C3%ADr%C3%AD%C3%A0
Àdúgbò Èkó, Ìpínlẹ̀ Èkó, Nàìjíríà
Ìtumò: Eyi je ibi ti nkan alaworan yip o sin i ilu Eko, nkan ti ounje “satellite” nitori náà ni won fi pee ni “Satellite Town”.
20231101.yo_2164_21
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%88k%C3%B3%2C%20%C3%8Cp%C3%ADnl%E1%BA%B9%CC%80%20%C3%88k%C3%B3%2C%20N%C3%A0%C3%ACj%C3%ADr%C3%AD%C3%A0
Àdúgbò Èkó, Ìpínlẹ̀ Èkó, Nàìjíríà
Ìtumò: saw mill jé lára àwon agbègbè tí ó tóbi jù tí wón ti máa n se ìtójú igi tí a fin kólé ìdí náà ni ó finjé saw-mill.
20231101.yo_2164_22
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%88k%C3%B3%2C%20%C3%8Cp%C3%ADnl%E1%BA%B9%CC%80%20%C3%88k%C3%B3%2C%20N%C3%A0%C3%ACj%C3%ADr%C3%AD%C3%A0
Àdúgbò Èkó, Ìpínlẹ̀ Èkó, Nàìjíríà
Ìtumò: “Salvation Avenue” je ibi ti awon elesin Christi posi “choistians”, ibi ti awon elesin bas i posi igbala ni won ma n pariwo (salvation) idi ti won fi n pe ni “salvation Avenue”
20231101.yo_2165_0
https://yo.wikipedia.org/wiki/Gb%C3%B3l%C3%B3h%C3%B9n%20Yor%C3%B9b%C3%A1
Gbólóhùn Yorùbá
'Gbólóhùn èdè Yorùbá ni a lè pè ní odidi ọ̀rọ̀ tí ó pé, tí ó ní olùṣe ati abọ̀ nínú tí ó sì bẹ̀rẹ̀ pẹ̀lú lẹ́tà ńlá. Síńtáàsì ni èka kan nínú gírámà èdè tí ó níí sè pèlú bi a se ń so òrò pò tí ó fi ń di gbólóhùn àti bí a se ń fún gbólóhùn yìi ní ìtumò. Síntáàsì ní òfin ìlànà ti elédè máa ń tèlé nígbà tí ó bá ń so èdè rè yí yàtò si ìlò èdè. Ìmò èdè ni ohun tí elédè mò nípa èdè rè sùgbón ìlò èdè ni ohun ti elédè so jáde ní enu. Elédè lè se àsìse nípa ìlò èdè sùgbón eléyìi kò so pé elédè yìí kò mo èdè rè. Òpò ìgbà ni ènìyàn làákàyè elédè sá féré bóyá látaàrí òhún jíje tàbí mįmu ti ó le máa mú elédè so kántankàntan. Kì í se pé elédé yìí kò mo èdè rè mo, ó mò ón. Àsìse ìlò èdè ni ó ń se. Nìgbà ti opolo red bá padà sípò, yóò so òrò ti ó mógbón lówó.
20231101.yo_2165_1
https://yo.wikipedia.org/wiki/Gb%C3%B3l%C3%B3h%C3%B9n%20Yor%C3%B9b%C3%A1
Gbólóhùn Yorùbá
Ohun tí a pè ni òfin yìí ni bi elédè se ń so èdè rè bí ìgbà pé ó ń tèlé ìlànà kan. Fún àpeere, eni tí ó bá gbó èdè Yorùbá dáradára yóò mò pé (1a) ni ó tònà pe (1b) kò tònà,
20231101.yo_2165_2
https://yo.wikipedia.org/wiki/Gb%C3%B3l%C3%B3h%C3%B9n%20Yor%C3%B9b%C3%A1
Gbólóhùn Yorùbá
Ohun tí eléyìí ń fi hàn wá nipé ìlànà kan wà tí elédè ń tèlé láti so òrò pò tí yóò first di gbólóhùn. Irú gbólóhùn tí ó bá tèlé ìlànà tí elédè mò yìí ni a ó so pé ó bá òfin mu.
20231101.yo_2165_3
https://yo.wikipedia.org/wiki/Gb%C3%B3l%C3%B3h%C3%B9n%20Yor%C3%B9b%C3%A1
Gbólóhùn Yorùbá
O ye kì a tètè menu ba ìyàtò kan ti ó wà láàrin bíbá òfin mù àti jíjé àtéwógbà. Gbólóhùn lè wà ti yóò bá òfin mu sùgbon tí ó lè máà jé àtéwógbà fún àwon tí ń so èdè. Bíbófinmu níí se pèlú ìmò èdè; ìlò èdè ni jíjé ítéwógbà níí se pèlú. Fún àpeere, àwon kan lè so pé (2a) kò jé ìtéwógbà fún àwon wi pé (2b) ni àwon gbà wolé.
20231101.yo_2165_4
https://yo.wikipedia.org/wiki/Gb%C3%B3l%C3%B3h%C3%B9n%20Yor%C3%B9b%C3%A1
Gbólóhùn Yorùbá
Méjèèjì ni ó bófin mu nítorí méjèèjì ni a máa ń so nínú èdè Yorùbá. Ìyen ni pé méjèèjì ni ó wà nínú ìmò wa gégé bí eni tí ó gbó Yorùbá. Nínú ìlò ni àwon kan ti lè so pé òkan jé ìtéwógbà, èkejì kò jé ìtéwógbà. Èyí kò ni ǹ kan se pèlú pé bóyá gbólóhùn méjèèjì bófin mu tàbí won kò bófin mu. Ìmò elédè nípa èdè rè ni yóò je wá lógún nínú jùlo.
20231101.yo_2165_5
https://yo.wikipedia.org/wiki/Gb%C3%B3l%C3%B3h%C3%B9n%20Yor%C3%B9b%C3%A1
Gbólóhùn Yorùbá
Ó ye kí á mò wípé òhún àdámó ni èdè jé. Ènìkan kì í lo sí ilé-ìwé láti kó bí Wón tí ń so Èdè abínibí rè. Ohun tí a ń so ni pé bí ìrìn rinrìn se jé àbìnibì fún omo, béè náà ni èdè jé. Fún àpeere, tí kò bá sí ohun tí ó se omo, tí ó bá tó àkókò láti rìn yóò rìn. Kì í se pé enì kan pe omo gúnlè láti kó o ni èyi. Báyìi gélé náà ni èdè jé. Àdámó ni gbogbo ohun ti omo nílò fún èdè abínibí, ó ti wà lára rè. Kò sí èdè ti kò lè lo èyí fún sùgbón èdè ibi tí a bá bi omo sì ni yóò lo àwon ohun èlò yìí láti so.
20231101.yo_2165_6
https://yo.wikipedia.org/wiki/Gb%C3%B3l%C3%B3h%C3%B9n%20Yor%C3%B9b%C3%A1
Gbólóhùn Yorùbá
(2) Òrò àti Àpólà: Òrò ti a ba tòó pò ni ó ń di àpólà. Ó seé se kí àpólà jé òrò kansoso. Ìyen tí òrò yìí kò bá ní èyán. Fún àpeere, àpólà-orúko ni a fa igi sí ní ìdi ní (3a) àti (3b).
20231101.yo_2165_7
https://yo.wikipedia.org/wiki/Gb%C3%B3l%C3%B3h%C3%B9n%20Yor%C3%B9b%C3%A1
Gbólóhùn Yorùbá
Ìyàtò àpólà-orúko méjèèjì yìí ni pé òrò méjì ni ó wa nínú àpólà-orúko (APOR’ ni a ó má a pè é láti ìsinsìnyí lo) (3a); òrò-orúko àti èyán rè tí ó jé òrò-àpèjúwe (AJ ni a ó máa pe òrò-àpèjúwe). Ní (3b), òrò kansoso ni ó wà lábé APOR. Òrò yìí, òrò-orúko (OR ni a ó máa lò fún òrò-orúko) ni, APOR náà sì ni. Ìsòri-òrò méjo ni àwon tètèdé onígìrámà so pé ó wà nínú èdè Yorùbá. Ìsòrí òrò méjo yìí ni wón sì pín si Olùwà àti Kókó Gbólóhùn. Olùwà àti kókó gbólóhùn yìí ni àwa yóò máa pè ní APOR àti APIS (àpólà-ìse) nínú ìdánilékòó yìí. Ìyen nip é àwa yóò ya ìsòrì-òrò àti isé ti ìsòri yìí ń se sótò si ara won. Ìsòri ni APOR tí ó ń sisé olùwà tàbí àbò nínú gbólóhùn. Ìsòrí ni APIS ti ó ń sisé kókó gbólóhùn.
20231101.yo_2165_8
https://yo.wikipedia.org/wiki/Gb%C3%B3l%C3%B3h%C3%B9n%20Yor%C3%B9b%C3%A1
Gbólóhùn Yorùbá
3. Gírámà ti a ó lò: Gírámà ìyidà onídàro ti Chomsky ni a ó mú lò nínú isé yìí. Ohun tí ó fà á ti a ó fi mú gíràmà yìí lò nip é ó gbìyànjú láti sàlàyé ìmò àbinibí elédè nípa èdè rè. Gírámà yìí sàlàyé gbólóhùn oónna, gbólóhùn ti ó jé àdàpè ara won abbl. Gírámà yìí yóò lo òfin ti ó níye láti sàlàyé gbólóhùn tí kò niye.
20231101.yo_2165_9
https://yo.wikipedia.org/wiki/Gb%C3%B3l%C3%B3h%C3%B9n%20Yor%C3%B9b%C3%A1
Gbólóhùn Yorùbá
Òfin ìhun gbólóhùn ni a ń pe (4). Ohun tí àmì òfà yìí ń so ni pé kí á tún gbólóhùn (GB) ko ni APOR àti APIS. Ó ye kì á tètè so báyìí pé ohun tí ó wà nínú gbólógùn ju èyí lo. Ohun tí a máa ń rí nínú gbólóhùn gan-an ni (5).
20231101.yo_2165_10
https://yo.wikipedia.org/wiki/Gb%C3%B3l%C3%B3h%C3%B9n%20Yor%C3%B9b%C3%A1
Gbólóhùn Yorùbá
Àfòmó ni AF dúró fún. Òun ni a máa ń pè ní àsèrànwò-ìse télè. Abé rè ni a ti máa ń rí ibá (IB), àsìkò (AS), múùdù (M) àti ìbámu (IBM). A lè fi èyí hàn báyìí:
20231101.yo_2165_11
https://yo.wikipedia.org/wiki/Gb%C3%B3l%C3%B3h%C3%B9n%20Yor%C3%B9b%C3%A1
Gbólóhùn Yorùbá
Kì í se dandan kí èdè kan ní gbogbo mérèèrin yìí. Yorùbá kò ni àsìkò sùgbón ó ni ibá. A ó menu ba àfòmó dáadáa ní iwájú sùgbón kí a tó se èyí, e jé kí á sòrò nípa APOR àti APIS
20231101.yo_2230_0
https://yo.wikipedia.org/wiki/Adeb%C3%A1y%C3%B2%20Faleti
Adebáyò Faleti
Adébáyọ̀ Àkàndé Fálétí (tí wọ́n bí ní Ọjọ́ kẹrìndínlọ́gbọ̀n oṣù Kejìlá 1930) jẹ́ ọmọ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà, Akéwì , Olùkọ̀tàn, àti eléré orí-Ìtàgé, bákan náà ni ó tún jẹ́ oǹgbufọ̀ èdè Gẹ̀ẹ́sì sí èdè Yorùbá, ó sìn tún jẹ́ Omíròyìn orí Ẹ̀rọ asoro-ma-gbesi Radio, Olóòtú ètò orí Tẹlifíṣọ̀n TV, àti Olùdásílẹ̀ ilé-iṣẹ́ ẹ̀rọ Amóhùnmáwòrán àkọ́kọ́ ní ilẹ̀ Adúláwọ̀ Afíríkà tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ Western Nigeria Television (WNTV).
20231101.yo_2230_1
https://yo.wikipedia.org/wiki/Adeb%C3%A1y%C3%B2%20Faleti
Adebáyò Faleti
Adébáyọ̀ Fálétí náà ló ṣe ògbufọ̀ orin àmúyẹ orílẹ̀-èdè Naigerian National Anthem láti èdè Gẹ̀ẹ́sì sí èdè abínibí Yorùbá. Bákan náà ni ó tún ṣe oǹgbufọ̀ fún ohun tí Ààrẹ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà nígbà kan rí lásìkò Ológun, ìyẹn Ibrahim Babangida sọ, pẹ̀lú tí Ààrẹ-fìdíhẹ nígbà ayé Ológun kan rí Chief Ernest Shoneka, nípa lílo èdè Yorùbá tó gbámúṣé. Fálétí ti tẹ Ìwé-Atúmọ èdè Dictionary Yorùbá ní èyí tí ó ní àbùdá ògidì Yorùbá nínú. Adébáyọ̀ Fálétí ti gba onírúurú àmì-ẹ̀yẹ ìdánilọ́lá oríṣiríṣi nílẹ̀ yìí àti lókè Òkun pẹ̀lú.
20231101.yo_2230_2
https://yo.wikipedia.org/wiki/Adeb%C3%A1y%C3%B2%20Faleti
Adebáyò Faleti
Adebayo Faleti (1993) Omo Olókùn Esin Heinemann Educational Books (Nigeria) PLC. ISBN 978-129-231-8
20231101.yo_2232_0
https://yo.wikipedia.org/wiki/Il%C3%A9-If%E1%BA%B9%CC%80
Ilé-Ifẹ̀
Ifẹ̀ (, tabi Ilé-Ifẹ̀) jẹ́ orírun gbogbo ọmọ Oòduà ní ilẹ̀ Yorùbá ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà. Ilé-Ifẹ̀ wà ní Ìpínlẹ̀ Ọ̀ṣun. Ifẹ̀ sí ìlú Ìpínlẹ̀ Èkó je kilomita igba o le mejidinlogun (218) tí àwọn tí wọ́n jẹ́ olùgbé ibẹ̀ lápapọ̀ jẹ́ 509,813 níye.
20231101.yo_2232_1
https://yo.wikipedia.org/wiki/Il%C3%A9-If%E1%BA%B9%CC%80
Ilé-Ifẹ̀
Gẹ́gẹ́ bí ìtàn ṣe sọ, Ilé-Ifẹ̀ ni wọ́n dá sílẹ̀ pẹ̀lú àṣẹ Olódùmarè nígbà tí ó pàṣẹ fún Ọbàtálá kí ó wá láti dá ayé kí ilẹ̀ sì bẹ̀rẹ̀ sí ṇ́ fẹ̀ láti ibẹ̀ lọ káàkiri àgbáyé; ìdí nìyí tí wọ́n fi ń pe Ilé-Ifẹ̀ ní Ifẹ̀ Oòyè, ibi ojúmọ́ ti ń mọ́ wáyé. Àmọ́, Ifẹ̀ yí ni Ọbàtálá pàdánù rẹ̀ sọ́wó Odùduwà Atẹ̀wọ̀nrọ̀, èyí ni ó fàá tí fàá ká ja ṣe wà láàrín àwọn méjèèjì. Odùduwà ni ó bẹ̀rẹ̀ ìjọba ní Ifẹ̀, ní èyí tí àwọn ọmọ rẹ̀ gbogbo náà sì di adarí àti olórí ìlú ní ẹlẹ́ka-ò-jẹ̀ka ibi tí wọ́n tẹ̀dó sí káàkiri orílẹ̀ Yorùbá lóní. Gẹ́gẹ́ bí a ti kàá nínú ìtàn, Ọọ̀ni àkọ́kọ́ tí yóò kọ́kọ́ jẹ ní Ifẹ̀ ni ó jẹ́ ọmọ bíbí inú Odùduwà tí ó jẹ́ ọ̀kànlélógójì òrìṣà fúnra rẹ̀, nígbà tí Ọọ̀ni tí ó wà níbẹ̀ lọ́wọ́ lọ́wọ́ báyí jẹ́ Ọọ̀ni Adéyẹyè Ẹnìtàn Ògúnwùsì Ọ̀jájá Kejì(II) tí wọ́n jẹ ní ọdún 2015. Bákan náà ni Ilé-Ifẹ̀ ní ọ̀kànlélúgba òrìṣà tí wọ́n ma ń bọ ní ọjọ́ kọ̀ọ̀kan yípo ọdún.
20231101.yo_2232_2
https://yo.wikipedia.org/wiki/Il%C3%A9-If%E1%BA%B9%CC%80
Ilé-Ifẹ̀
Ilé-Ifè ìlú ńlá tí òkìkí rẹ̀ kàn jákè-jádò àgbáyé fún àwọn Iṣẹ́ ọnà wọn bíi ère orí Odùduwà àti àwọn ohun ọnà míràn tí wọ́n lààmì-laaka ní ǹkan bí ọdún 1200 àti 1400 A.D sẹ́yìn.
20231101.yo_2242_0
https://yo.wikipedia.org/wiki/K%E1%BB%8D%CC%81l%C3%A1%20Ak%C3%ADnl%C3%A0d%C3%A9
Kọ́lá Akínlàdé
A bí Kọ́lá Akínlàdé ní ọdún 1924, ní ìlú Ayétòrò ní ìpínlẹ̀ Ògùn ní ilẹ̀ Nàìjíríà. Àwọn òbí rẹ̀ ni Michel Akínlàdé àti Elizabeth Akínlàdé. Ó lọ sí ilé-ẹ̀kọ́ Pọ́ọ̀lù mímọ́ ní Ayétòrò. Lẹ́yìn tí ó parí ẹ̀kọ́ rẹ̀ ní ilé-ẹ̀kọ́ yìí ni ó kọjá sí Ìlaròó tí ó sì dá iṣẹ́ tẹ̀wétẹ̀wé sílẹ̀ ńbẹ̀ fúnrarẹ̀ ni ó ka ìwé gba ìwé-èrí G.C. E. ní ilé.
20231101.yo_2242_1
https://yo.wikipedia.org/wiki/K%E1%BB%8D%CC%81l%C3%A1%20Ak%C3%ADnl%C3%A0d%C3%A9
Kọ́lá Akínlàdé
Lẹ́yìn tí Kọ́lá Akínlàdé gba ìwé-ẹ̀rí yìí ni ó dá ìwé ìròyàn kan sílẹ̀ tí ó pe orúkọ rẹ̀ ní ‘Ẹ̀gbádò Progressive Newspaper: Lẹ́yìn èyí ni ó wá bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ gẹ́gẹ́ bi akọ̀wé ìjọba. Ó ṣiṣẹ́ lábẹ́ ìjọba ìpínlè ìwọ̀-oòrùn àtijọ́ ní ilẹ̀ Nàìjíríà.
20231101.yo_2242_2
https://yo.wikipedia.org/wiki/K%E1%BB%8D%CC%81l%C3%A1%20Ak%C3%ADnl%C3%A0d%C3%A9
Kọ́lá Akínlàdé
Kị́lá Akínlàdé lọ kàwé ní Yunifásítì Ifẹ̀ ní ilẹ̀ Nàìjíríà ó sì tún padà sí ẹnu iṣẹ́ ní ìpínlẹ̀ ìwọ̀-oòrùn Nàìjíríà. Ní ọdún 1976 ni Kọ́lá Akínlàdé fẹ̀yìn tì. Ní ọdún 1980, ó tún gba iṣẹ́ olùkọ́ sí ìbàdàn Boys High School, Ìbàdàn, Nàìjíríà. Ó wá fi ẹ̀yìn tì ní ọdún 1984. Kọ́lá Akínlàdé ní ìyàwó ó sì bí ọmọ.
20231101.yo_2242_3
https://yo.wikipedia.org/wiki/K%E1%BB%8D%CC%81l%C3%A1%20Ak%C3%ADnl%C3%A0d%C3%A9
Kọ́lá Akínlàdé
Lára wọn ni Ajá to ń Lépa Ẹkùn, Ọ̣wọ̣̣́ Tẹ Amòokùnṣìkà, Àgbákò nílé Tẹ́tẹ́, Baṣọ̀run Olúyọ̀lé, Ajayi, the Bishop, Chaka, the Zulu, Esther, the Queen, Abraham, The…..Friend of God, Sheu Usman Dan fodio, Òwe àti Ìtumọ̀ rẹ̀, Sàǹgbá fọ́, àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ. Ó sì tún kópa nínú kíkọ Àsàyàn Ìtàn.
20231101.yo_2242_4
https://yo.wikipedia.org/wiki/K%E1%BB%8D%CC%81l%C3%A1%20Ak%C3%ADnl%C3%A0d%C3%A9
Kọ́lá Akínlàdé
1. Ọmọ ilé-èkọ́ ni Dúró Orímóògùnjé. Ó ku Ọdún kan kí ó jáde ìwé mẹ́wàá. Ìyá rẹ̀ kú ní ọdún mẹ́ta sẹ́yìn, ìyẹ̀n ni pé ó kú ní ọdún mẹ́ta ṣáájú bàbá rẹ̀. Ọmọ ọgọ́ta ọdún ni Bàbá rẹ̀ nígbà tí ó kú. Ikú bàbá rẹ̀ tí ó gbọ́ ní ilé-ẹ̀kọ́ ni o gbé e wálé. Ìyàwó mẹ́rin ni Àkàndé Orímóògùnjẹ́ tí ó jẹ́ ìyá Dúró ti kú, ó ku mẹ́ta. Ọmọ márùn-un ni Àkàńgbé Orímóògùnjé bí Dúró sì ni àgbà gbogbo wọn. Òun ni àkọ́bí. Ìyaa folúké, ọ̀kan nínú àwọn ìyàwó wọ̀nyí, ni ìríjú àkándé, Orímóògùnjẹ, ìyẹn ni pé òun ni ó fẹ́ran jù. Ìya fólúké yìí ni ó mú kọ́kọ́rọ́ séèfù jáde tí ó ṣí i tí wọn kò sì bá nǹkan kan ní ibẹ̀. Ìgbà tí Àkàndé mú owó kẹ́yìn nínú séèfù yìí kí ó tó kú, owó tí ó wà nínú rẹ̀ ju ẹgbàáta náírà (N30,000.00)lọ. Ọ̀gbẹ́ni Ajúṣefínní: Òun ní ó ra kòkó lówó Àkàngbé. Ó sanwo ní 10/2/80.
20231101.yo_2242_5
https://yo.wikipedia.org/wiki/K%E1%BB%8D%CC%81l%C3%A1%20Ak%C3%ADnl%C3%A0d%C3%A9
Kọ́lá Akínlàdé
Àṣàkẹ́: Òun ni ó jẹ́rìí sí owó kòkó ti Àkàngbé gbà. Ohun tí ó yani lẹ́nu ni pé Ogóje náírà (N140.00) péré ni wọ́n bá ní abẹ́ ìrọ̀rí Àkàngbé nígbà tí ó kú.
20231101.yo_2242_6
https://yo.wikipedia.org/wiki/K%E1%BB%8D%CC%81l%C3%A1%20Ak%C3%ADnl%C3%A0d%C3%A9
Kọ́lá Akínlàdé
2. Túnde Atọ̀pinpin náà kọ lẹ́tà sí Olófìn-íntótó. Ìdẹ̀ra ni orúkọ ilé-ẹ̀kọ́ àbúrò Túndé Atọ̀pinpin. Ọmọ ọdún mẹ́tàdínlógún ni Dúró orímóògùnjẹ́. Ẹ̀gbọ́n Ilẹ́sanmí ni Àdùnní ìyá Dúró Orímóògùnjẹ́. Àgbẹ̀ oníkòkó ni Àkàngbé orímóògùnjẹ́, bàbá Dúró nígbà ayé rẹ̀. Túndé Atọ̀pinpin àti ẹ̀gbọ́n rẹ̀ máa ń sùn ní ilé Àkàngbé nígbà ti wọ́n bá ń lọ sí ìhà Odò Ọya. Dúró Orímóògùnjẹ́ nìkan ni ọmọ tí Àdùnní bé. Ará ìlú Àdùnní ni Olófìn-íntótó, ọmọ Adéṣínà. Túndé Atòpinpin máa ń lọ gbé ojà ní Èkó. Ọkọ̀ ojú omi ni ọjà yìí máa ń bá dé.
20231101.yo_2242_7
https://yo.wikipedia.org/wiki/K%E1%BB%8D%CC%81l%C3%A1%20Ak%C3%ADnl%C3%A0d%C3%A9
Kọ́lá Akínlàdé
3. Olófìn-íntótó, ọmọ olusínà kọ̀wé sí Túndé Atọ̀pinpìn. Àròsọ ni Olófin-íntótó àti ilésanmí ti wokò. Dírẹ́bà wọn ń sáré gan-an ni. Fìlà Olófìn-íntótó tilẹ̀ sí sọ̀nù ní ọ̀nà. Ó dá mọ́tọ̀ dúró ni kí ó tó lọ mú un Nígbà tí wọ́n dé ojà, dírébà jẹ ẹ̀bà, ilésanmí jẹ iyán ó sì ra òòyà ní irinwó náírà (400.00)
20231101.yo_2242_8
https://yo.wikipedia.org/wiki/K%E1%BB%8D%CC%81l%C3%A1%20Ak%C3%ADnl%C3%A0d%C3%A9
Kọ́lá Akínlàdé
Ní ọjà, Olófìn-íntótó bá obìnrin kan pàdé. Ó ra ọtí fún un. Obìnrin yìí sì mu ìgò otí kan tán ó sì mu ìkejì dé ìdajì. Ó yẹ kí a sẹ àkíyèsí obìnrin yìí dáadáa nítorí pé òun nì a wá fi hàn gẹ́gẹ́ bí ẹni tí ó jí owó Àkàngbé Orímóògùnjẹ́ jí ní iwájú.
20231101.yo_2242_9
https://yo.wikipedia.org/wiki/K%E1%BB%8D%CC%81l%C3%A1%20Ak%C3%ADnl%C3%A0d%C3%A9
Kọ́lá Akínlàdé
Nígbà ti Olófìn-íntótó àti Ilésanmí dé Ilé-Ifè tí wọn ń lọ, ọ̀dọ̀ Àlàó ni wọ́n dé sí. Ilé-Ifẹ̀ ni Àlàó ti ń ta ojà. Àlàó ra obì àti ọtí fún Olófìn-íntótó Olófìn-íntótó mu bíà mẹ́ta. Àlàó ń mu ẹmu lẹ́yìn tí ó jẹun tán Ilésanmú sì ń mu ògógóró. Ọlọ́fìn-íntótó gbádùn láti máà fi ọwọ́ pa túbọ̀mu rẹ̀. Irun tí ó hù sí orí ètè òkè ní ìsàlẹ̀ ibi tí imú wà ni ó ń jẹ́ túbọ̀mu. Àsàkẹ́: Ó jẹ́ ọ̀kan nínú àwọn ìyàwó Àkàngbé Orímóògùnjẹ́. Gbajímọ̀ ènìyàn ni. Ọmọ ọgbọ̀n ọdún ni ṣùgbọ́n ó dàbí ọmọ ọdún mọ́kànlélógún. Ọ̀mọ̀wé ni.
20231101.yo_2242_10
https://yo.wikipedia.org/wiki/K%E1%BB%8D%CC%81l%C3%A1%20Ak%C3%ADnl%C3%A0d%C3%A9
Kọ́lá Akínlàdé
Yéwándé: Ọ̀kan nínú àwọn ìyàwó Àkàngbé ni òun náà. Kò kàwe ṣùgbọ́n o ní ọ̀yàyà ó sì máa ń ṣe àyẹ́sí ènìyàn.
20231101.yo_2242_11
https://yo.wikipedia.org/wiki/K%E1%BB%8D%CC%81l%C3%A1%20Ak%C3%ADnl%C3%A0d%C3%A9
Kọ́lá Akínlàdé
Àlàó: Òun ni Olófin-íntótó àti Ilésanmí dé sí ọdọ rẹ̀. Onígbàgbọ́n ni. Jọ̀ọ́nú ni orúkọ rẹ̀ mìíràn. Ó máa ń gbàdúrà ni alaalé kí ó tó sùn. Ọmọ mẹ́ta ni ó bí. Ní ọjọ́ tí àwọn Olófin-íntótó kọ́kọ́ dé ilé rẹ̀ tí wọ́n ń gbàdúrà ó ní kí gbgbo wọn kọ orin wá bá mì gbé olúwa. Àwọn ọmọ Àlàó kò bá wọn kọ ẹsẹ kejì tí ó sọ wí pé ‘Ọjọ́ ayéè mi ń sáré lọ sópin’. Àsàmú tí ó jẹ́ ọ̀kan nínú àwọn ọmọ Àlàó ni ó ṣe àlàyé fún bàbá rẹ̀ ìdí tí wọn kò ṣe kọ ẹsẹ kejì orin náà. Ó ní orin àgbàlagbà ni.
20231101.yo_2242_12
https://yo.wikipedia.org/wiki/K%E1%BB%8D%CC%81l%C3%A1%20Ak%C3%ADnl%C3%A0d%C3%A9
Kọ́lá Akínlàdé
4. Ilésanmí rọ́ àlà tí ó lá fún Akin Atọ̀pinpin ọmọ Olúṣínà. Ó ní nínú àlá tí òun lá, òún. Rí ẹni tí ó gbé owó ṣùgbọ́n òun kò rí ojú rẹ̀ tí òun fi ta jí. Ẹ jẹ́ kí á ṣe àkíyèsí àwọn nǹkan wọ̀nyí tí wọ́n mẹ́nu bà ní orí yìí.
20231101.yo_2242_13
https://yo.wikipedia.org/wiki/K%E1%BB%8D%CC%81l%C3%A1%20Ak%C3%ADnl%C3%A0d%C3%A9
Kọ́lá Akínlàdé
Ọládúpọ̀ - - Ọmọ Àkàngbé Orímóògùnjé ni òun náà. Ọmọ ọdún mẹ́fà ni. Ilé-ẹ̀kọ kékeré ni ó wà. Fólúkẹ́, Omówùmí àti Oládípọ̀ jẹ́ ọmọ Yẹ́wándé. Bándélé jẹ́ ọmọ odún méje. Àṣakẹ́ ni ó bíí Yàtọ̀ sí Àkàngbé Orímóògùnjẹ́, Yéwándé nìkan ni ó tún máa ń mu owó nínú séèfù. Àìsàn Orímóògùnjẹ́ kò ju ọjọ́ mẹ́wàá lọ tí ó fi kú.
20231101.yo_2242_14
https://yo.wikipedia.org/wiki/K%E1%BB%8D%CC%81l%C3%A1%20Ak%C3%ADnl%C3%A0d%C3%A9
Kọ́lá Akínlàdé
Ilé Orímóògùnjẹ́ kò ju ilé kẹ́rin lọ sí ilé Àlàó. Nígbà tí àwọn Olófìn-íntótó dé ilé Orímóògùnjẹ́ láti bẹ̀rẹ̀ ìwádìí. Yéwándé ni ó mú wọn wọlé Kọ́kọ́rọ́ ojú ńlá séèfù yìí kìí ya Orímóògùnjẹ́. Abẹ́ ìrọ̀rí rẹ̀ ni ó wà nígbà tí ó ń ṣàìsàn. Kì í yọ kọ́kọ́rọ́ ojú kékeré séèfù.
20231101.yo_2242_15
https://yo.wikipedia.org/wiki/K%E1%BB%8D%CC%81l%C3%A1%20Ak%C3%ADnl%C3%A0d%C3%A9
Kọ́lá Akínlàdé
Àṣàkẹ́ wọlé bá wọn níbi tí wọn ti ń sọ̀rọ̀ níbi tí wọ́n ti ń ṣe ìwádìí nílé Orímóògùnjẹ́. Wọ́n máa ń há ìlẹ̀kùn yàrá Orímóògùnjẹ́ ṣùgbọ́n wọ́n máa ń fi kọ́kọ́rọ ibẹ̀ há orí ìtérígbà. Ẹnikẹ́ni ní inú ilé ni ó lè mú un ní ibẹ̀ kí ó sì fi sí ilẹ̀kùn
20231101.yo_2242_16
https://yo.wikipedia.org/wiki/K%E1%BB%8D%CC%81l%C3%A1%20Ak%C3%ADnl%C3%A0d%C3%A9
Kọ́lá Akínlàdé
Yéwándé ni ó máa ń tọ́jú Orímóògùnjẹ́ lóru nígbà tí ó ń ṣe àìsàn. Àṣàkẹ́ máa ń ràn án lọ́wọ́. yéwándé àti àwọn ọmọ náà máa ń wá tọ́jú Orímóògùnjẹ́ nígbà ti ó ń ṣàìsàn lọ́wọ́ tí àìsàn rẹ̀ bá ń yọnu.
20231101.yo_2242_17
https://yo.wikipedia.org/wiki/K%E1%BB%8D%CC%81l%C3%A1%20Ak%C3%ADnl%C3%A0d%C3%A9
Kọ́lá Akínlàdé
Àlàó ni ó kó ogóje náírà (N140.00) tí wọ́n bá níbi ìgbèré Orímóògùnjẹ́ fún Yéwándé láti tójú. Orúkọ mìíràn tí Àkàngbé Orímóògùnjẹ́ tún ń jẹ́ ni Bándélé. Ẹ rántí pé eléyìí yàtọ̀ sí Bándélé orúkọ ọ̀kan nínú àwọn ọmọ rẹ.
20231101.yo_2242_18
https://yo.wikipedia.org/wiki/K%E1%BB%8D%CC%81l%C3%A1%20Ak%C3%ADnl%C3%A0d%C3%A9
Kọ́lá Akínlàdé
Ọ̀sanyìnnínbí ni orúkọ oníṣèègùn Orímóògùnjẹ́. Ó ra páànù ìgàn méjìlá ní ọ̀dọ̀ kékeréowó. Èyí sì fẹ́ mí ìfura dání nítorí owó tí ó sonù. Àwọn kan rò pé bóyá òun ni ó jí owó Orímóògùnjẹ́ tí ó sọnù.
20231101.yo_2242_19
https://yo.wikipedia.org/wiki/K%E1%BB%8D%CC%81l%C3%A1%20Ak%C3%ADnl%C3%A0d%C3%A9
Kọ́lá Akínlàdé
Nílé Orímóògùnjẹ́ níbití wọ́n ti ń ṣe ìwádìí, Ọlọ́fìn-íntótó rí ẹ̀já òwú kan tí ó wà lára ọ̀kan nínú àwọn ojú kéékèèkéé inú séèfù ó sì mú un. Gbòngán ni fọláṣadé ìyàwó àfẹ́kẹ́yìn Orímóògùnjẹ́ ń gbé. Ó máa ń lò tó ọjọ́ márùn-ún tàbí ọ̀sẹ̀ kan ní ifẹ̀ ní ilé Orímóògùnjẹ́ kí ó tó padà sí Gbọ̀ngán. Kò bímọ kankan fún Orímóògùnjé. Ó yẹ kí a ṣe àkíyèsí fọláṣadé dáadáa nítorí pé òun ni Olófìn-íntótó ra otí fún ní ọjà tíó mu ìgò ọtí kan àbò. Òun ni a sì rí ní òpin ìwé pé òun ni ó jí owó Orímóògùnjẹ́ gbé.
20231101.yo_2242_20
https://yo.wikipedia.org/wiki/K%E1%BB%8D%CC%81l%C3%A1%20Ak%C3%ADnl%C3%A0d%C3%A9
Kọ́lá Akínlàdé
5. Ọmọ́tọ́ṣọ̀ọ́ ní sítọ́ọ̀. Káyọ̀dé ni orúkọ akọ̀wé rẹ̀. Ó ti tó ọdún mẹ́fà kí Akin Ọlọ́fín-íntótó ọmọ Olúṣínà àti Ọmọ́tọ́ṣọ̀ọ́ ti rí ara wọn mọ kí wọn tún tó rí ara wọn yìí. Àbúrò Orímóògùnjẹ́ ni Ilésanmí tí òun àti Olófìn-íntótó jọ wá ṣe ìwádìí ní ilé-Ifè. Ọ̀rẹ́ Orímóògùnjẹ́ ni Ajíṣefínní tí ó ń ta kòkó. Bíọlá ni orúkọ ẹni tí ó ń ta ọtí
20231101.yo_2242_21
https://yo.wikipedia.org/wiki/K%E1%BB%8D%CC%81l%C3%A1%20Ak%C3%ADnl%C3%A0d%C3%A9
Kọ́lá Akínlàdé
Lóòótọ́, oníṣèègùn ni Ọ̀sanyìnnínbí síbẹ̀, kò wọ ẹgbẹ́ àwọn Oníṣèègùn tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ Ẹgbẹ́ ìlera loògùn Ọrọ̀.
20231101.yo_2242_22
https://yo.wikipedia.org/wiki/K%E1%BB%8D%CC%81l%C3%A1%20Ak%C3%ADnl%C3%A0d%C3%A9
Kọ́lá Akínlàdé
Ilésanmí àti Ọlọ́fin-íntótó sọ nípa ara wọn pé àwọn mọ ilẹ̀ tẹ̀ múyẹ́ (Ẹ rántí pé iṣẹ́ ọ̀tẹlẹ̀lmúyẹ́ ni wọ́n ń ṣe). Ajúṣefínní, ọ̀rẹ́ orímóògùnjẹ́ ni ó bá Orímóògùnjẹ́ ra ilẹ̀ tí ó ń kọ́ ilé sí. A ó rántí pé kòkó ní Ajíṣefínní ń tà.
20231101.yo_2242_23
https://yo.wikipedia.org/wiki/K%E1%BB%8D%CC%81l%C3%A1%20Ak%C3%ADnl%C3%A0d%C3%A9
Kọ́lá Akínlàdé
Ọwọ́ Òṣúnlékè ni wọ́n ti r ailẹ̀ tí Orímóògùnjẹ́ fi ń kólé náà. Ẹgbẹ̀ta náírà (N600.00) ni wọ́n ra ilẹ̀ náà.
20231101.yo_2242_24
https://yo.wikipedia.org/wiki/K%E1%BB%8D%CC%81l%C3%A1%20Ak%C3%ADnl%C3%A0d%C3%A9
Kọ́lá Akínlàdé
Káyòdé akòwé Ọmọ́tọ́ṣọ̀ọ́ sùn ní ẹnu iṣẹ́ Ìgbà tí wọ́n bi í pé kí ló dé tí ó fi sùn ni ó dáhùn pé olè ajẹ́rangbe tí àwọn ń lé ní òru ni kò jẹ́ kí àwọn sùn dáadáa. Ó yẹ kí á ṣe àkíyèsí pé Oníṣèègùn Ọ̀sanyìnnínbí ni olórí àwọn olè ajẹ́rangbé yìí gẹ́gẹ́ bí a ó ṣe rí i kà ní iwájú. Ẹran tí ó ń jí gbé yìí wà lára ohun tí ó jẹ́ kí àwọn ènìyàn fura sí Ọ̀sanyìnnínbí pé òun ló jí owó Orímóògùnjẹ́ gbé níbi tí ó tí ń tọ́jú rẹ̀ nígbà tí ó ń ṣe àìsàn.