_id
stringlengths
17
21
url
stringlengths
32
377
title
stringlengths
2
120
text
stringlengths
100
2.76k
20231101.yo_2127_29
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A0d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%ACl%C3%BA%20%C3%8Cb%C3%A0d%C3%A0n
Àwọn àdúgbò ìlú Ìbàdàn
Ìtumò: Ilé eléégún tí ó ń jé afìdi èlégèé ni ó wà ní àdúgbò náà, tí ó sì ní orúko ńlá ní ìlú Ìbàdàn. Àti pé ibè ni wón ti máa ń se àseye fún eni tó bá kú tí kìí se elésìn mùsùlùmí tàbí ìgbàgbó.
20231101.yo_2127_30
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A0d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%ACl%C3%BA%20%C3%8Cb%C3%A0d%C3%A0n
Àwọn àdúgbò ìlú Ìbàdàn
Ìtumò: Àgbègbè tí bale kan tó n jé Olúgbòde ni ìlú Ìbàdàn láyé àtìjó kólé sí ni a ń pè ni Ìta-baálè lónì yìí.
20231101.yo_2127_31
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A0d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%ACl%C3%BA%20%C3%8Cb%C3%A0d%C3%A0n
Àwọn àdúgbò ìlú Ìbàdàn
Ìtumò: Akinkanjú ológun kan un ó di Odò láye àfìjó nígbà tí àwon òdá rè fé mu. Ó wòó pé kàkà kí ilè kú ilè á sá. Ìdí nìyí tí wón fi so Odò náà ni kúde tì láti máa fi se ìrántí akoni náà, tí gbogbo agbègbè náà sì di kúdetì bákan náà.
20231101.yo_2127_32
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A0d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%ACl%C3%BA%20%C3%8Cb%C3%A0d%C3%A0n
Àwọn àdúgbò ìlú Ìbàdàn
Ìtumò: Agbègbè kan tí àwon ènìyàn tí ogun lé kùró ní ìbùgbé won tèdó sí, tí wón sì fin í ìsinmi ni a ń pè ni Ináléndé lónì yìí.
20231101.yo_2127_33
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A0d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%ACl%C3%BA%20%C3%8Cb%C3%A0d%C3%A0n
Àwọn àdúgbò ìlú Ìbàdàn
Ìtumò: Egúngún ni lá olókìkí kan wà ilú Ìbàdàn tí kìí pojú kan Obìnrin. Agbègbè tí ilé eni tí maa ń gbé eégún náa wà ni a ń pè ní Òde-ajé Olóòlù sì ni orúko egúngún náà ní Òde-ajé-Olóòtù.
20231101.yo_2127_34
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A0d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%ACl%C3%BA%20%C3%8Cb%C3%A0d%C3%A0n
Àwọn àdúgbò ìlú Ìbàdàn
Ìtumò: Okùnrin kan wà láyè àtíjó tó ní n àsìn bíi adìye ati eyele, okùnrin yìí sì fún je eni tó burú púpò. Bákan náà, okùnrin yìí féràn àgbàdo púpò. Gbogbo ìgbà tí ó bá fi ń fun àwon ń nkan òsìn rè lóńje, ni oùn náà máà ń je àgbàdo ti rè. Nítorí ìwà yìí, àwon ènìyàn máa ń júwe ìlé rè gégé bíi bàbá-a-bá-eye-rún-oka bàbà. Báyìí ni wón se só ó di Béyerúnkà.
20231101.yo_2127_35
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A0d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%ACl%C3%BA%20%C3%8Cb%C3%A0d%C3%A0n
Àwọn àdúgbò ìlú Ìbàdàn
Ìtumò: Agbègbè yìí jé ibi ti òwò èkùr’’o pípa wópò sí. Ìdí nìyí tí won fi so àdúgbò náà ní elékùró.
20231101.yo_2127_36
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A0d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%ACl%C3%BA%20%C3%8Cb%C3%A0d%C3%A0n
Àwọn àdúgbò ìlú Ìbàdàn
Ìtumò: Agbègbè yìí ni bàbá tí ó máa ń bo òrìsà òkè-Ìbàdàn ń gbé. Ìdí nìyí tí won fi ń pe àdúgbò náà ni ìlé abòkè.
20231101.yo_2127_37
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A0d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%ACl%C3%BA%20%C3%8Cb%C3%A0d%C3%A0n
Àwọn àdúgbò ìlú Ìbàdàn
Ìtumò: Agbegbe tí àwon ènìyàn, tí ogun lé kúrò níbì kan, tí gbogbo wón sì ro gìlàgìlà dé sí ni a ń pè ní Dùgbè
20231101.yo_2127_38
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A0d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%ACl%C3%BA%20%C3%8Cb%C3%A0d%C3%A0n
Àwọn àdúgbò ìlú Ìbàdàn
Ìtumò: Ìtàn fi yé wa pé Òkan léhìn àwon omo Ogun Bashorun Ìbíkúnlé tí ó jé jagun-jagun pàtàkì ní ìlú Ìbàdàn ní ó ńgbé àdúgbò yìí. Nítorí àkíkanjú rè lójú ogun tú won fi ńpè ni amúló ju ogun. Ìnagije yìí sì ni won so di Amunigun
20231101.yo_2127_39
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A0d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%ACl%C3%BA%20%C3%8Cb%C3%A0d%C3%A0n
Àwọn àdúgbò ìlú Ìbàdàn
Ìtumò: Ibí jé àgó àwon abìrun kan, àwon odi ni wón máa ńkó síbè fún ìtójú, ní ayé àtijó ilé-ìtóju odi ní ibè jé.
20231101.yo_2127_40
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A0d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%ACl%C3%BA%20%C3%8Cb%C3%A0d%C3%A0n
Àwọn àdúgbò ìlú Ìbàdàn
Ìtumò: Ní àyé àtijó oko obì ní wón fi adúgbò yìí dá àwon àgbè alóko osì ní ó ńgbé ìbè tí o fí jé wípé tí ènìyàn bá ńlo abé obì ni yío màà tò lo.
20231101.yo_2127_41
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A0d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%ACl%C3%BA%20%C3%8Cb%C3%A0d%C3%A0n
Àwọn àdúgbò ìlú Ìbàdàn
Ìtumò: Okùnrin kán wà ní àdúgbò tí féràn láti máa je àgbàdo, ni ìgbà yen àwon àgbe ka àgbàdo kún oúnje ye nítori, ìdí èyí ní wón se ńjè Okùnrin náà ní eni tí ó ń bá èye rú Okà.
20231101.yo_2127_42
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A0d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%ACl%C3%BA%20%C3%8Cb%C3%A0d%C3%A0n
Àwọn àdúgbò ìlú Ìbàdàn
Ìtumò: Ìnagije alàgbà tí ó jé baákì àdúgbò yìí rí, tí ò si je oloro pèlu oun ti eni àkoko láti dé àdúgbò yìí.
20231101.yo_2127_43
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A0d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%ACl%C3%BA%20%C3%8Cb%C3%A0d%C3%A0n
Àwọn àdúgbò ìlú Ìbàdàn
Ìtumò: Àwon àgbà fí yé wá pé awuye wuye kún tí ó wáyé láàrín àwon elegbé ode lórí ode tí ó tédòó láti de igbó yìí. Orúko àdúgbò yìí gan ni “Igbódìjà”
20231101.yo_2127_44
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A0d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%ACl%C3%BA%20%C3%8Cb%C3%A0d%C3%A0n
Àwọn àdúgbò ìlú Ìbàdàn
Ìtumò: Ìtàn yíì dá lórí okùnrin kan tí ó yá owó sùgbón tí kò lè singbà nípasè àíró wó san, ó dá ìgbà àti dá owó yìí padà sùgbón kò ri san.
20231101.yo_2127_45
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A0d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%ACl%C3%BA%20%C3%8Cb%C3%A0d%C3%A0n
Àwọn àdúgbò ìlú Ìbàdàn
Ìtumò: Igbó ni àdúgbò yí jé ní ayé Ìgbà yen, àwon ará àdúgbò yìí ni wón béèrè sì nà ojà alé ní bè Ìdí nà yí tí orúko àdúgbò yìí fi wáyé.
20231101.yo_2127_46
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A0d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%ACl%C3%BA%20%C3%8Cb%C3%A0d%C3%A0n
Àwọn àdúgbò ìlú Ìbàdàn
Ìtumò: Igi kúnwá nì àdúgbò ewé aréré ni ó maa ń wù lórí rè, ewé yìí máa ńtàn tí o fi sé wípé Ibòji ré pò púpò, ìwon ènìyàn máa ńjoko láti gba ategùn níbè won sì máà ń se fàájì níbì pèlú.
20231101.yo_2127_47
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A0d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%ACl%C3%BA%20%C3%8Cb%C3%A0d%C3%A0n
Àwọn àdúgbò ìlú Ìbàdàn
Ìtumò: Nkan ti o mu oriko adugbo yii wa nipe adapo yangi ati ile erofo ni olorun da ibe, o sit un je oke, Ibe maa n nira lati gba.
20231101.yo_2127_48
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A0d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%ACl%C3%BA%20%C3%8Cb%C3%A0d%C3%A0n
Àwọn àdúgbò ìlú Ìbàdàn
Ìtumò: Ibi yíi ni awon oyinbo ajele gbe aremo Alaafin Oya sa pamo si ki o maa ba ku lehin Iku baba re gere bi asa awon Oyo.
20231101.yo_2127_49
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A0d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%ACl%C3%BA%20%C3%8Cb%C3%A0d%C3%A0n
Àwọn àdúgbò ìlú Ìbàdàn
Ìtumò: Àdúgbò yìí jé ibi tí won ní orúkí asiwájú kan ni akoko kan ni Ibadan tí orúko rè ń jé Ológbéńlá. Ológbéńlá yìí ni wón wá so di “Gbenla”èka-èdè ló fà á
20231101.yo_2127_50
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A0d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%ACl%C3%BA%20%C3%8Cb%C3%A0d%C3%A0n
Àwọn àdúgbò ìlú Ìbàdàn
Ìtumò: A gbó pé ni àsìkò ogun Ìbàdàn àti ìjàyè, owó àwon ìjàyè ló kókó dun àwon Ìbàdàn ti won sì mu olórí ogun Ìbàdàn ìgbà náà sí ìgbèkùn won. Àwon omo-Ogun Ìbàdàn padà sí ilé láti lo tún ara mu, won sì padà ìjàyè ni àkókó yìí ni Ibàdàn ségun Ìjàyè pátápatá tí wón mú lérú Okàn àwon Ìbàdàn kò bale nígbà tí wón dé ilé nítorí èèyàn líle ni awon ìjàyè ìdí nìyí tí wón fi wá yan àwon òpò omo-ogun won sí ojú ònà tí àwon ìjàyè mó ó ń rìn wo Ìbàdàn, lásìkò ìgbà náà láti máa só won. A gbó pé àwon omo-ogun wònyí lò to osù méta dáádáá kíwon tó kúrò níbè, ni wón fi so ògangan ibè ni Alékúsó (ibi tí a gbé uan eeyan kó máa so won).
20231101.yo_2127_51
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A0d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%ACl%C3%BA%20%C3%8Cb%C3%A0d%C3%A0n
Àwọn àdúgbò ìlú Ìbàdàn
Ìtumò: Ojà kan ló wà nì adúgbò yìí tó jé wí pé kìkì àlùbósà nì wón máa ń tà, ní bè gégé bí isé ajé won. Ibikíbi ní àwon ìlú tó wà léti Ìbàdàn sin i won ti máa ń wá ra àtùbósà tó bá ti je enì tó fé ra òpò.
20231101.yo_2127_52
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A0d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%ACl%C3%BA%20%C3%8Cb%C3%A0d%C3%A0n
Àwọn àdúgbò ìlú Ìbàdàn
Ìtumò: Àbúrò ni eni tó/te/ Ode-Ajé olóòlù yìí jé sí eni tó te àdúgbò òde-Ajé alálùbósà dó ó, kó tó di ojà. A gbó pé jagunjagun ni wón àti wí pé eégún Olóòlù yìí òkan lára erù ti wón ko bò láti ojú-ogun ni. Ègbón ló ní kí àbúlò òun sún sí ìsàlè díè kí ó tó dúró, èyí ló fà á tí àdúgbò mejeeji yìí kò fi jìnnà si ara won.
20231101.yo_2127_53
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A0d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%ACl%C3%BA%20%C3%8Cb%C3%A0d%C3%A0n
Àwọn àdúgbò ìlú Ìbàdàn
Ìtumò: Àdúgbò yìí ń be láàrin òjé sí yemétu Ìdí tí wón fi ń pè é ni Òkè-Àpón ni pé òke-kere ni àdúgbò òhún wà tó sì takété sí títì lákòókò kan àwon tí kò tíì ni Ìyàwó nílé nì wón máa ń sáábà gba tàbí réǹtì ilé sí àdúgbò yìí, pàápàá àwon omo ile-ìwé èkósé Nóòsì ti na ìwe èkóse noosí tiko jinna sibe àti àwon òsìsé sekiteríàtì. Nítorí pé àwon òdó wá po níbè tíwon kò sì tíì ni ìyàwó tàbí oko ni won fi so àdúgbò yìí ní òkè-Àpón. Tí àwon olóńje bíi èbà, iyán fùfú èwà àti béèbéè/ lo bá ti apé ońje lé omo won lórí fún kíkiri, won á wà so fún-un pé kó tètè mó o gbé ojà rè lo oke-Àpón nítorí ojà, pàápàá ońje, a máa tà níbè púpò.
20231101.yo_2127_54
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A0d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%ACl%C3%BA%20%C3%8Cb%C3%A0d%C3%A0n
Àwọn àdúgbò ìlú Ìbàdàn
Ìtumò: Abénà ìmò mi so pé àwon ará Ìbàdàn gbèjà Ìbikúnle tó jé Balógun won ní àkókò ken pé wón wá ta òtúu rè lójì (ojì -> gbèsè tàví fáìnì) wón wá so pé ibi ti baba won ìyen (ìbíkúnlé) gbé sanwo ojì náà ni won ń pè ni Agbeni ìdí nìyí tíwón fi máa ń ki àwon Ìbàdàn ní “Agbeniníjà omo òkè Ìbàdán
20231101.yo_2127_55
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A0d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%ACl%C3%BA%20%C3%8Cb%C3%A0d%C3%A0n
Àwọn àdúgbò ìlú Ìbàdàn
Ìtumò: Àdúgbò yìí jé bí oríta tó ya ìlú ìjàyè àti Òyó sótò ní Ìbàdàn. Ìdí nip é ni Móníyá nì èèyàn tó ń lo sí ìlú ìjàyè yóò ti yà. Ní ojó ti àwon ará Ìbàdàn/wá ń lo sógun ìjàyè nígbà tí won dé móníyá wón pín ara won àwon kan yà sí ona tó gba ìjàyè lo tààrà, àwon kan gba ojú ònà òyó lo láti lè gba fìdítì wo ìjàyè Ògúnmólá ni wón so pé, ó sájú Ogun lódún náà, wón ní Ìbíkúnlé ò lo “Ibi ti gbogbo wa ti yà là ń pè ní Móníyà”
20231101.yo_2127_56
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A0d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%ACl%C3%BA%20%C3%8Cb%C3%A0d%C3%A0n
Àwọn àdúgbò ìlú Ìbàdàn
Ìtumò: Lójó tí àwon Ìbàdàn ń lo Ogun Èkìtì parapò ti àwon omo ogun tó jé akoni wa kó ara won jo sójú kan tí won ró gégé kí won ó tó wa ránsé re ilé Balógun Ìbíkúnlé pé kó máa bò pé àwon ti se tán ni “Gégé” “Won ró gégé-tan won ranse re ilé Balógun won”.
20231101.yo_2127_57
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A0d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%ACl%C3%BA%20%C3%8Cb%C3%A0d%C3%A0n
Àwọn àdúgbò ìlú Ìbàdàn
Ìtumò: Nígbà tí wón ń lo ogun Èkìtì parapò yìí wón ní ó pé won díè ki wón ó tó fi ìlú Ìbàdàn sí ilè nítorí won kò múra fún ogun yìí, òjíjì ni won rónísé Alaafin kí omo ogun tó ye kó lo, ó tó múra tán ó pe díè. Ibì tó wà gbé ló won jáí púpò kí won ó tó fi odi ìlú sílè ni wón so nì “òde-òóló”.
20231101.yo_2127_58
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A0d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%ACl%C3%BA%20%C3%8Cb%C3%A0d%C3%A0n
Àwọn àdúgbò ìlú Ìbàdàn
Ìtumò: Láyé ìgbà kan, Okùnrin ìjèsà kan wà nì ìlú. Ìbàdàn tó jé pé ó máa ń sòsómàáló. Okùnrin yìí gbajúmò púpò aso-òkè ló máa ń tà. Ní ojó kan owó rè wá bó sonù, ó wa owó yìí títí, kò ri, bàbá yìí wá bèrè sì í ké nitori owo yìí ká a lára, owó tó ti ń pa á bò láti àárò ni ‘Òwó bó, Olá bó, ìbòòsí àrè” Ibi tówó bàbá ìjèsà gbé bó sonù là ń pè nì “Lábó”
20231101.yo_2127_59
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A0d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%ACl%C3%BA%20%C3%8Cb%C3%A0d%C3%A0n
Àwọn àdúgbò ìlú Ìbàdàn
Ìtumò: Àdúgbò yìí ni won ti máa ń pín àgbá ota fún àwon omo-ogun Ìbàdàn tí wón bá ń lo ogun. Ibi ti won ti rí yíta Ogun fún wa ni “Eléta”
20231101.yo_2127_60
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A0d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%ACl%C3%BA%20%C3%8Cb%C3%A0d%C3%A0n
Àwọn àdúgbò ìlú Ìbàdàn
Ìtumò: Abénà-ìmó mi so fun mi pé ibi ti won ti yé àwon eni àkókó sí ni ayéyé. Òkan lára àwon tí wón yé sí nígbà náà lóhùn-ún nì “Agbájé Ayéyé “Ibi tí a gbé yéni sí là ń pè láyéyé”.
20231101.yo_2127_61
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A0d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%ACl%C3%BA%20%C3%8Cb%C3%A0d%C3%A0n
Àwọn àdúgbò ìlú Ìbàdàn
Ìtumò: Láyé ijóun, tí wón bá fe lo sí ogun ní ìlú Ìbàdàn, Balógun yóò se ìkéde láti pé àwon ode, olóògùn ológun tó bá dára rè lójú tó fé bá won lo sójú ogun. Nígbà tí gbogbo àwon èèyàn wòn yí ba péjú sìbà, ni Balógun àti àwon ìjòyè rè yòókù yóò tó wá á sa àwon to pójú-òsùwòn láti lo léhìn òpò Ìdánrawò. Òpóyéosà ni gbangba ibi tí wón ti máa ń se èyí Níbàdàn wà nitori ko jinnà si ilé Balógun. Irú èyí náà selè nínú ìwé Ògbójú Ode nínú Igbó Irúnmolè tí D.O. Fágúnwà ko. Ibi tí a gbe n sa won lójó tá a bá n lo ogun là ń pè ni yéosà nijo-un.
20231101.yo_2127_62
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A0d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%ACl%C3%BA%20%C3%8Cb%C3%A0d%C3%A0n
Àwọn àdúgbò ìlú Ìbàdàn
Ìtumò: Wón ní ìná ló lé àwon ènìyàn tówà ní àdúgbò yìí dé ibè láyé ijóun. Wón wá so pé ní àdúgbò odinjo ni iná ti sé lójó náà, èyí fíhàn pé àwon tó sá kúrò níbè tí won kò padà síbè mó ni won so ibè ni orúko ìtumò re nip é (Ní-hàà-ín ní iná lémi dé)
20231101.yo_2127_63
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A0d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%ACl%C3%BA%20%C3%8Cb%C3%A0d%C3%A0n
Àwọn àdúgbò ìlú Ìbàdàn
Ìtumò: Lójó ti iyò wón ti gbogbo Ìbàdàn àti ìlú agbègbè rè kó rí iyò je tàbí se Obè. Ológbó tawón pé iyò pé iyò wà nì ìkòròdú lébàá Èkó ni gbogbo Ìbàdàn bá to jánà rere bí esú jáko. Ìyá baba mi máa ń pe odún náà ní “Odún gágá”. Nígbà tí wón wá n padà bò látìkòròdú, Ìdí Arere ni àwon èrò kókó gbé sò. Níjó èrò ìbàdàn n wayo o rekorodu tí gbogbo wón to jánà rere bi esú jáko, ìdí Arere lakokoso èrò”
20231101.yo_2127_64
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A0d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%ACl%C3%BA%20%C3%8Cb%C3%A0d%C3%A0n
Àwọn àdúgbò ìlú Ìbàdàn
Ìtumò: Òòsà-oko nì won máa ń bon i àdúgbò yìí Níbàdàn. Àwon Oloosa oko ló wà ní bè títí di òní. Awoni ènìyàn a sì máa lo toro omo níbè
20231101.yo_2127_65
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A0d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%ACl%C3%BA%20%C3%8Cb%C3%A0d%C3%A0n
Àwọn àdúgbò ìlú Ìbàdàn
Ìtumò: Àgó-odi-ìlú ló di Agodi nítorí èhìn odi ìlú ni àdúgbò yìí wà láyé àtijó Níbàdàn Ibè si ni ilé-isé Telifísòn àkókó wà nítorí ìbè máa ń dáké róró ni.
20231101.yo_2127_66
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A0d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%ACl%C3%BA%20%C3%8Cb%C3%A0d%C3%A0n
Àwọn àdúgbò ìlú Ìbàdàn
Ìtumò: Àdúgbò yìí ni àwon ìjo Àgùdà fi Ìbùjokòó sí nígbà tí wón dé pèlú èsìn won páàdi ni wón máa ń pe àwon olórí èsìn yìí.
20231101.yo_2127_67
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A0d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%ACl%C3%BA%20%C3%8Cb%C3%A0d%C3%A0n
Àwọn àdúgbò ìlú Ìbàdàn
Ìtumò: Bàbá kan ni ó máa ń dá oko sí èbá ìdí Ìrókò ní àtijó. Ìgbàkúùgbà tí wón bá ti ń wá bàbá yí tàbí wón fé gba nǹken lówó rè, wón á ní kí won lo wò ó ní Ìdí-Ìrókò. Bí bàbá yí se kó abúlé síbè nìyí àti ìgbà yìí ni wón ti ń pe ibè ní ìdí Ìrókò.
20231101.yo_2127_68
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A0d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%ACl%C3%BA%20%C3%8Cb%C3%A0d%C3%A0n
Àwọn àdúgbò ìlú Ìbàdàn
Ìtumò: Òyìnbó kátólíìkì ni a gbó pé ó kó ilé rè si orí okè kàn ti àwon ènìyàn sì máa ń wo ilé náà lórí òkè téńté ríí wón bá wá béèrè pé níbo ni enìkan ń lo o le ni ibi tí sápátì kólé kólé si. Bí wón se so ibid i òkè sápátì nìyí
20231101.yo_2128_0
https://yo.wikipedia.org/wiki/Or%C3%BAk%E1%BB%8D%20%C3%80d%C3%BAgb%C3%B2%20n%C3%AD%20%E1%BB%8C%CC%80f%C3%A0%2C%20%C3%8Cp%C3%ADnl%E1%BA%B9%CC%80%20Kw%C3%A1r%C3%A0%2C%20N%C3%A0%C3%ACj%C3%ADr%C3%AD%C3%A0
Orúkọ Àdúgbò ní Ọ̀fà, Ìpínlẹ̀ Kwárà, Nàìjíríà
Ìtumò: Agbègbè yìí ni àwon ìdílé Oba máa ń de ilè àti ìdòtí sí ni ayé atijo. Sùgbón ìgbà tí ó yá ni ilé bèrè sí ní dé àdúgbò yíí. Bí wón se ń pe àdúgbò yìí ní Atan Oba.
20231101.yo_2128_1
https://yo.wikipedia.org/wiki/Or%C3%BAk%E1%BB%8D%20%C3%80d%C3%BAgb%C3%B2%20n%C3%AD%20%E1%BB%8C%CC%80f%C3%A0%2C%20%C3%8Cp%C3%ADnl%E1%BA%B9%CC%80%20Kw%C3%A1r%C3%A0%2C%20N%C3%A0%C3%ACj%C3%ADr%C3%AD%C3%A0
Orúkọ Àdúgbò ní Ọ̀fà, Ìpínlẹ̀ Kwárà, Nàìjíríà
Ìtumò: Ní àyé àtijó àwon ara àdúgbò yìí máa ń gun igi obì láti ká obì, nítorí wón gbà pé obì yìí máa ń mówó wólé. Èyí ni àwon ènìyàn rí tí wóm fi so àdúgbò yìí ní apónbì
20231101.yo_2128_2
https://yo.wikipedia.org/wiki/Or%C3%BAk%E1%BB%8D%20%C3%80d%C3%BAgb%C3%B2%20n%C3%AD%20%E1%BB%8C%CC%80f%C3%A0%2C%20%C3%8Cp%C3%ADnl%E1%BA%B9%CC%80%20Kw%C3%A1r%C3%A0%2C%20N%C3%A0%C3%ACj%C3%ADr%C3%AD%C3%A0
Orúkọ Àdúgbò ní Ọ̀fà, Ìpínlẹ̀ Kwárà, Nàìjíríà
Ìtumò: Igi ń lá kán wà ni agbègbè yìí tí àwon eye lékeléke máa ń bà le. Gbogbo àwon ilé tí ó wà níbè ni àwon lékelékèé yìí máa ń yàgbé sí tí asogbo ara ilé náà á sì funfun. Sùgbón ìgbà tí olájú wá dí òfà ni wón kó àgó olópàá sí àdúgbò yíi. Tí wón bá ti wá fe júwe àgó olópàá yìí wón máa ń so wi pe àdúgbò funfun leye ń sun. Bí orúko yìí se mó won lára títí dóní nìyí.
20231101.yo_2129_0
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A0d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%ACl%C3%BA%20M%E1%BB%8Dd%C3%A1k%E1%BA%B9%CC%81k%E1%BA%B9%CC%81
Àwọn àdúgbò ìlú Mọdákẹ́kẹ́
Ìtumò: Onísòwò ni gbogbo won. nínú oríkì won lo ti jáde tói so pé. Kárí kárà kámó sanwó, ká sin owó kó dìjà
20231101.yo_2129_1
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A0d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%ACl%C3%BA%20M%E1%BB%8Dd%C3%A1k%E1%BA%B9%CC%81k%E1%BA%B9%CC%81
Àwọn àdúgbò ìlú Mọdákẹ́kẹ́
Ìtumò: Orúko Eégún to maa ń jáde ni agboile yìí ni. Nínú oríki rè ló ti jáde tó so pé. Elébiti sàgbá ko níjà.
20231101.yo_2129_2
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A0d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%ACl%C3%BA%20M%E1%BB%8Dd%C3%A1k%E1%BA%B9%CC%81k%E1%BA%B9%CC%81
Àwọn àdúgbò ìlú Mọdákẹ́kẹ́
Ìtumò: Orò ni won ń bò. Àwon ara agbo ilé yìí máa ń dásà pe bi obìnrin bá fojú di orò, orò yóò gbe e.
20231101.yo_2129_3
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A0d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%ACl%C3%BA%20M%E1%BB%8Dd%C3%A1k%E1%BA%B9%CC%81k%E1%BA%B9%CC%81
Àwọn àdúgbò ìlú Mọdákẹ́kẹ́
Ìtumò: Oti títà ni isé owó won. Eléyìí hàn nínú oríkì won tó sap é: Játi jákà bí àdèbà Oti sèkètè ni won máa ń se
20231101.yo_2129_4
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A0d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%ACl%C3%BA%20M%E1%BB%8Dd%C3%A1k%E1%BA%B9%CC%81k%E1%BA%B9%CC%81
Àwọn àdúgbò ìlú Mọdákẹ́kẹ́
Ìtumò: Ní àtijo òrìsà kan wà ni ibi tí à ń pè ni ìráyè yìí orúko òrìsà náà ni ìrá láti ipólé òwu ni wón ti gbé òrìsà yìí wá léyìn ogun húkù húkù, obaláayè ni orúko àwòro rè. Bí wón bat i n bo òrìsà yìí tí won da Obì tí Obì si yàn àwon Olùsìn rè yóòmáa pariwo ayò pé ìra ti yè, Ìráyè, ìráyè láti ibi yìí ni a ti mu orúko àdúgbò yìí
20231101.yo_2129_5
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A0d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%ACl%C3%BA%20M%E1%BB%8Dd%C3%A1k%E1%BA%B9%CC%81k%E1%BA%B9%CC%81
Àwọn àdúgbò ìlú Mọdákẹ́kẹ́
Ìtumò: Ìrísí ìyá ken tí ó jé gbajúmò ni agbo ilé yìí ni won fi n pè é ìyá náà lówó lówó béè ni ó sì pupa wèè ó sì tún sígbonlè pípupa tí ìyà yìí pupo ni won fi n fi àwò rè júwe rè tí wón si fi so agbo ilé yìí
20231101.yo_2129_6
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A0d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%ACl%C3%BA%20M%E1%BB%8Dd%C3%A1k%E1%BA%B9%CC%81k%E1%BA%B9%CC%81
Àwọn àdúgbò ìlú Mọdákẹ́kẹ́
Ìtumò: Àwon ìran oníkòyí ni wón te agbo ilé yìí dó, jagunjagun sin i wón àwon ni won máa n jagun fun ìlú.
20231101.yo_2129_7
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A0d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%ACl%C3%BA%20M%E1%BB%8Dd%C3%A1k%E1%BA%B9%CC%81k%E1%BA%B9%CC%81
Àwọn àdúgbò ìlú Mọdákẹ́kẹ́
Ìtumò: Ilé Alésinlóyè ni won máa n pè é télè kí won fi n pe béè ni pé okùnrin ken wa níbè nígbà náà tí ó máa n gun esin ni àsìkò ilé odún tí wón bá wa sí ilé láti oko àsìkò yìí sì ni oyé máa n mu ni agbègbè wa; èyí ni won fi máa n pè é ni Alésin nígbà oyé.
20231101.yo_2129_8
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A0d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%ACl%C3%BA%20M%E1%BB%8Dd%C3%A1k%E1%BA%B9%CC%81k%E1%BA%B9%CC%81
Àwọn àdúgbò ìlú Mọdákẹ́kẹ́
Ìtumò: Aji bá esin lórí òòró ni wón sún kid i ajíbésinró. Ní àtijó àwon ìdílé yìí ni won máa n fie sin rin ìrìn àjò béè wón sì ni esin yìí to pò gan-an débi pe won máa n so won mólè ní iwájú ìta nit í eni tí ó ń lo tí o ń bò yóò máa ba won níbè.
20231101.yo_2129_9
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A0d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%ACl%C3%BA%20M%E1%BB%8Dd%C3%A1k%E1%BA%B9%CC%81k%E1%BA%B9%CC%81
Àwọn àdúgbò ìlú Mọdákẹ́kẹ́
Ìtumò: Àwon ènìyàn tí ogun lé kúrò ni ìpólé òwu nígbà ogun húkùhúkù ni wón tèdó si ibí, orúko ìlú won ni won si fib o agbolé won
20231101.yo_2129_10
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A0d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%ACl%C3%BA%20M%E1%BB%8Dd%C3%A1k%E1%BA%B9%CC%81k%E1%BA%B9%CC%81
Àwọn àdúgbò ìlú Mọdákẹ́kẹ́
Ìtumò: Níbí yìí ni ilè ìjósìn àkókó ni ilú Modákéké kókó wa àwon ìjo sítifáánù mimó ni wón kó ilé ìjósìn yìí bákan náà légbèé rè ni ilé ìjósìn àwon mùsùlùmí wà èyí ni won fi so Ibè ni ita ìsìn èyí tí ó wa di itaàsìn
20231101.yo_2129_11
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A0d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%ACl%C3%BA%20M%E1%BB%8Dd%C3%A1k%E1%BA%B9%CC%81k%E1%BA%B9%CC%81
Àwọn àdúgbò ìlú Mọdákẹ́kẹ́
Ìtumò: Ìnágije babaláwo kan ni ń jé báyìí ìdí ti wón fi n pè é béè ni pé babaláwo náà máa n tu eni ti àwon àjé bá dè mólè béè ni ó sì máa n gbogbo kùrukùn ti bá n be ní ìgbésí ayé omo èdá. Babalawo náà gbónà ìlú mo ká sì nib í àwon ènìyàn ba ti n lo si ilé rè won a ni àwon ènìyàn ba ti n lo si ilé rè won a ni àwon n lo si ilé arídìíèké èyí ni won fi n pe agbe ilé yìí di òní olónìí
20231101.yo_2129_12
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A0d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%ACl%C3%BA%20M%E1%BB%8Dd%C3%A1k%E1%BA%B9%CC%81k%E1%BA%B9%CC%81
Àwọn àdúgbò ìlú Mọdákẹ́kẹ́
Ìtumò: Ìdì ti wón fi ń pe agbo ilé yìí ni ilé eréta ni pé níògangan agbo ilè yìí ni àwon ará ijóhun ti máa n wa ota tí àwon alágbède máa n yó sínú ìgbá kí won ó tó so ó di Irin ti won fi n rokó ròdá.
20231101.yo_2129_13
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A0d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%ACl%C3%BA%20M%E1%BB%8Dd%C3%A1k%E1%BA%B9%CC%81k%E1%BA%B9%CC%81
Àwọn àdúgbò ìlú Mọdákẹ́kẹ́
Ìtumò: Ìsé ìlù lílù ni wón n se níbí ìlù bàtá ni won sì máa n lù àwon onílù ìdílè yìí ni wón máa n lu bàtà fun àwon tí won ń bo òrìsà sàngó àti àwon eléégún ibé owó won yìí ni won fi so agbo ilé won loruko.
20231101.yo_2129_14
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A0d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%ACl%C3%BA%20M%E1%BB%8Dd%C3%A1k%E1%BA%B9%CC%81k%E1%BA%B9%CC%81
Àwọn àdúgbò ìlú Mọdákẹ́kẹ́
Ìtumò: Orúko enìkàn tí ó jé gbajúmò ní ìlù Modákéké ni ó ń jé Amólà ní àgbègbè Ibi tí ó kó ilé sí òkè yí. Ibè po ni béè ni orí òkè yìí ni ó kó ilé sí tente èyì ni won fi n pe agbo ilé yìí ni òkè Amolà
20231101.yo_2129_15
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A0d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%ACl%C3%BA%20M%E1%BB%8Dd%C3%A1k%E1%BA%B9%CC%81k%E1%BA%B9%CC%81
Àwọn àdúgbò ìlú Mọdákẹ́kẹ́
Ìtumò: Látijo isé aró dídà ni àwon idílè yìí máa n se isé yìí ni àwon ènìyàn sì mo wón mó bí enìkàn bá ti fe lo si ilé won, won á ni àwon ń lo sí ilé aláró, orúko yìí ni wón tè mo agbo ilé yìí lára dòní olónìí.
20231101.yo_2129_16
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A0d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%ACl%C3%BA%20M%E1%BB%8Dd%C3%A1k%E1%BA%B9%CC%81k%E1%BA%B9%CC%81
Àwọn àdúgbò ìlú Mọdákẹ́kẹ́
Ìtumò: Níbí ni igbódù àwon baba awo kí ilù ó to máa fè si nígbà tí ìlú wá kúrò ni inú igbó ni àwon babalawo wá fenu kò pé ibè ni àwon yòó ti máa se ìpàdé owo àwon yóò lo se igbódù mìíràn ni wón bá n se ìpàdé awo ni òkè awo. Èyí ni won fi ń pe ibè ní òkè awo di òní.
20231101.yo_2129_17
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A0d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%ACl%C3%BA%20M%E1%BB%8Dd%C3%A1k%E1%BA%B9%CC%81k%E1%BA%B9%CC%81
Àwọn àdúgbò ìlú Mọdákẹ́kẹ́
Ìtumò: Ní agbo ilé yìí ni won ti máa n ta àgbàdo ju ní àsìkò òjò èyí rí béè torí pé àwon kíì sábà gbin oúnje mìíràn àfi àgbàdo ìdí nìyí ti won fi n pè won ni ilé àtàgbàdo òjò.
20231101.yo_2129_18
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A0d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%ACl%C3%BA%20M%E1%BB%8Dd%C3%A1k%E1%BA%B9%CC%81k%E1%BA%B9%CC%81
Àwọn àdúgbò ìlú Mọdákẹ́kẹ́
Ìtumò: Odò ti ó ń sun láti ilè tí won wa gbé ape le lórí láti inú àpe yìí ni won ti máa n pon omi yìí idí nìyí ti wón fi so ni agbo ilé olomi ape.
20231101.yo_2129_19
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A0d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%ACl%C3%BA%20M%E1%BB%8Dd%C3%A1k%E1%BA%B9%CC%81k%E1%BA%B9%CC%81
Àwọn àdúgbò ìlú Mọdákẹ́kẹ́
Ìtumò: Orita ni àdúgbò yi jé títì mérin ni wón sì pàdé níbè èyí ló fà á tí wón fi n pè é ni ìtamérin.
20231101.yo_2129_20
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A0d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%ACl%C3%BA%20M%E1%BB%8Dd%C3%A1k%E1%BA%B9%CC%81k%E1%BA%B9%CC%81
Àwọn àdúgbò ìlú Mọdákẹ́kẹ́
Ìtumò: Ní agbe ilé yìí – isé gbegilére ni isé won àwon ìdílé Ajibógun ni won sì máa n gbénà ni wón ba kúkú so ìdílé náà ní ilé gbénàgbénà sùgbón akekúrú rènì àwon ènìyàn ń pè dòní
20231101.yo_2129_21
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A0d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%ACl%C3%BA%20M%E1%BB%8Dd%C3%A1k%E1%BA%B9%CC%81k%E1%BA%B9%CC%81
Àwọn àdúgbò ìlú Mọdákẹ́kẹ́
Ìtumò: Ìtàn ìgbà ìwásè so fun wa pe tokotaya kan wà níbí agbo ilé yìí tí won n bí àbìkú omo bí won bat i bi omo yìí ni yóòkú ni won wá pinnu láti kó omo tí wón bi ni àsìkò kan jade kí won ó si se ináwó rè kí ayé gbó kórun mò. Nìgbà tí wón se báyìn ni omo bá dúró ni kò bá kú mó èyí ni ó fà á ti won fi so ibè ni kóìíwò èyí tí àpajá rè ń jé kó èyí wò ná bóyá a jé dúró.
20231101.yo_2129_22
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A0d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%ACl%C3%BA%20M%E1%BB%8Dd%C3%A1k%E1%BA%B9%CC%81k%E1%BA%B9%CC%81
Àwọn àdúgbò ìlú Mọdákẹ́kẹ́
Ìtumò: Ìtàn so pé Ibè ni (District officer) ń gbé orí òkè sì ni ibè ilé àwon tí ó ti di ipò D.O. yìí mu ti wón jé òyìnbó sì wà níbè pèlú. Léyìn ìgbà tí a gba òmìníra àwon òyìnbo ti ń gbé ibè kí Obásanjó ó tó sòfin kí àlejò m;aa lo ní (1978)
20231101.yo_2129_23
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A0d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%ACl%C3%BA%20M%E1%BB%8Dd%C3%A1k%E1%BA%B9%CC%81k%E1%BA%B9%CC%81
Àwọn àdúgbò ìlú Mọdákẹ́kẹ́
Ìtumò: Àwon ìdílè yìí jé ìdílé tí wón wa láti ede wá tèdó sí Modákéké. Ilá ni wón sì máa ń gbìn. Wón ni wón máa n sòrò pé ilá odun yìí o àkálà ni o ohun tí wón máa n wí yìí ni won fi so agbo ilé won ni ilé àkálà.
20231101.yo_2129_24
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A0d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%ACl%C3%BA%20M%E1%BB%8Dd%C3%A1k%E1%BA%B9%CC%81k%E1%BA%B9%CC%81
Àwọn àdúgbò ìlú Mọdákẹ́kẹ́
Ìtumò: Télètélè rí, àwon eléégún ni àwon ti wón ń jé alágbàáà yìí ibè sì ni àwon olórí òjè won wa. lénu kan kìkìdá àwon eléégún ni wón dá àdúgbò yìí sílè.
20231101.yo_2129_25
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A0d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%ACl%C3%BA%20M%E1%BB%8Dd%C3%A1k%E1%BA%B9%CC%81k%E1%BA%B9%CC%81
Àwọn àdúgbò ìlú Mọdákẹ́kẹ́
Ìtumò: Ní ayé àtijó, ode niwón nínú agboolé yìí Akíkanjú ènìyàn sì ni wón nínú ode sisé nígbà náà, tí wón bá degbó lo títí tí wón bá pa erankéran àwon ni wón máa ń gbé orí rè fún. Ìdi rè nìyí tí wón fi ń pè wón ní agbóríitú.
20231101.yo_2129_26
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A0d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%ACl%C3%BA%20M%E1%BB%8Dd%C3%A1k%E1%BA%B9%CC%81k%E1%BA%B9%CC%81
Àwọn àdúgbò ìlú Mọdákẹ́kẹ́
Ìtumò: Gégé bí wón ti so, wón ní láti Ilésà ni àwon tí ó da àdúgbò yìí sílè ti wá. Nítorí pá àwon ìjèsà ni a máa ń kì ni “Omo owá, obokun rémi”.
20231101.yo_2129_27
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A0d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%ACl%C3%BA%20M%E1%BB%8Dd%C3%A1k%E1%BA%B9%CC%81k%E1%BA%B9%CC%81
Àwọn àdúgbò ìlú Mọdákẹ́kẹ́
Ìtumò: Gbogbo àwon tí wón kólé ládúgbò yìí ni wón femu kò láti so àdúgbò won ni Ìrépòlérè. A lè so pé pèlú ìsòkan tí wón ní ni orúko àdúgbò yìí se di
20231101.yo_2129_28
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A0d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%ACl%C3%BA%20M%E1%BB%8Dd%C3%A1k%E1%BA%B9%CC%81k%E1%BA%B9%CC%81
Àwọn àdúgbò ìlú Mọdákẹ́kẹ́
Ìtumò: Ìtàn so fún wa pé, àwon tó wà ni àdúgbò yìí láyé àtijó jé ologbón gidigidi, tó fi jé pe tí òrò bá rújú tan níbò míràn àwon ni wón máa ń báwon dá eyó pèlú. Èyí ló mú kí àwon aládùúgbò won panupò so àdúgbò yìí dó títí di òní olónìí yìí.
20231101.yo_2129_29
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A0d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%ACl%C3%BA%20M%E1%BB%8Dd%C3%A1k%E1%BA%B9%CC%81k%E1%BA%B9%CC%81
Àwọn àdúgbò ìlú Mọdákẹ́kẹ́
Ìtumò: Ní ayé àtijó àwon babaláwo ni wón wa ní àdúgbò yìí. Ní ìgbà náà gbogbo wa mò pé ipa pàtàkì ni Ifá ń kó láwùjò àwon Yorùbá, èyí ló mú kí àwon ènìyàn máa so pé, àwon ń lo sílé baba awo títí wón fi so ó di ilé Awótóbi.
20231101.yo_2129_30
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A0d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%ACl%C3%BA%20M%E1%BB%8Dd%C3%A1k%E1%BA%B9%CC%81k%E1%BA%B9%CC%81
Àwọn àdúgbò ìlú Mọdákẹ́kẹ́
Ìtumò: Ìdí tí wón fi ń pe àdúgbò yìí ni Amókèegùn nip é, kí èègùn tó débè yóò gun òkè bíi mélòó kan, lénu kan òkè ni a máa gùn débè ni wón se so àdúgbò ni Amókèegùn.
20231101.yo_2129_31
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A0d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%ACl%C3%BA%20M%E1%BB%8Dd%C3%A1k%E1%BA%B9%CC%81k%E1%BA%B9%CC%81
Àwọn àdúgbò ìlú Mọdákẹ́kẹ́
Ìtumò: Ìsé àwon àdúgbò yìí ni wón se so wón lórúko. Ní ayé àtijó làálì tí àwon Hausa máa ń lé sórí èékánná ni àwon fi ń sisé se ní ti won. Idí nìyí tí wón fi ń pè wón ní ilé Onílàálì.
20231101.yo_2129_32
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A0d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%ACl%C3%BA%20M%E1%BB%8Dd%C3%A1k%E1%BA%B9%CC%81k%E1%BA%B9%CC%81
Àwọn àdúgbò ìlú Mọdákẹ́kẹ́
Ìtumò: Ní ayé àtijó ìtàn kan so fún wa pé àwon tí wón wa nínú agbo ilé yìí gbáfínjú dáadáa, kò sí ibi tí wón lè dé nígbà náà tí wònkò ní mò pé inú àdúgbò yìí ni wónm ti jáde wá, ni àwon ènìyàn se pa emu pò láti so wón ni ilé Ogérojú.
20231101.yo_2129_33
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A0d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%ACl%C3%BA%20M%E1%BB%8Dd%C3%A1k%E1%BA%B9%CC%81k%E1%BA%B9%CC%81
Àwọn àdúgbò ìlú Mọdákẹ́kẹ́
Ìtumò: Wón ni ní ìgbà ken Igbó tí ouni máa wa lára rè ni ènìyàn máa wà dé àdúgbò yìí, àárò kùtù hàn ni omi yìí máa ń wà ní ara igbó yìí tó fi jé pé kò sí bí ènìyàn se lè jí lo sì àdúgbò yìí ki aso irú eni béè ma tutu wálé. Idí nìyí tí wón fi so àdúgbò yìí ni agbón-an-ni.
20231101.yo_2129_34
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A0d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%ACl%C3%BA%20M%E1%BB%8Dd%C3%A1k%E1%BA%B9%CC%81k%E1%BA%B9%CC%81
Àwọn àdúgbò ìlú Mọdákẹ́kẹ́
Ìtumò: Ní ilé yìí, àwon jagunjagun má fit i ìbon se ni wón, tí ogun bale tán won ki í lo ìbon láti fi jà rárá bí kò se kùmò àti ada pèlú ida. Ko sì sí bí ogun náà se lè le tó ti wón lè pa wón lójú ogun, fóniladìe toko èèmó bò nit ì won. Ìdí nìyí tí wón fi ń pè wón ní ilé Atólógun.
20231101.yo_2129_35
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A0d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%ACl%C3%BA%20M%E1%BB%8Dd%C3%A1k%E1%BA%B9%CC%81k%E1%BA%B9%CC%81
Àwọn àdúgbò ìlú Mọdákẹ́kẹ́
Ìtumò: Ìtàn so fún wa pé àwon tó wà ni ilé Àgbójà máa ń bínú púpò tó fi jé pet í enìkan bá yan ènìyàn je lójú won, wón lè so ìjà náà di ti won pátápátá, kò sì sí ibi tí wón ti lè gbá pé wón ń jà ní àdúgbò tó tì wón, tí won kò ní débè láti loo jà. Òpèbé aríjà sorò ló mú won di ìlé àgbójà.
20231101.yo_2129_36
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A0d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%ACl%C3%BA%20M%E1%BB%8Dd%C3%A1k%E1%BA%B9%CC%81k%E1%BA%B9%CC%81
Àwọn àdúgbò ìlú Mọdákẹ́kẹ́
Ìtumò: Isé owó tí wón ń se ló mú ki wón máa pe àdúgbò won ni òsúnaró. Isé aró rife ni wón fi sísé òjó won, bí ó tilè jé pé isé aró ríre yìí kò wópò láàrin won mó
20231101.yo_2129_37
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A0d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%ACl%C3%BA%20M%E1%BB%8Dd%C3%A1k%E1%BA%B9%CC%81k%E1%BA%B9%CC%81
Àwọn àdúgbò ìlú Mọdákẹ́kẹ́
Ìtumò: Nínú agbo ilé yìí láyé àtijó, wón ní àwon omo agbo ilé yìí máa ń wéré nígbà náà, èyí ló mú kí won máa pe agbo ilé won ní ilé léwèéré.
20231101.yo_2129_38
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A0d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%ACl%C3%BA%20M%E1%BB%8Dd%C3%A1k%E1%BA%B9%CC%81k%E1%BA%B9%CC%81
Àwọn àdúgbò ìlú Mọdákẹ́kẹ́
Ìtumò: Wón ni inú àwon tí ń gbé àdúgbò yìí té púpò, won kì í ba èèyàn jà rárá, wón sì máa n ba èèyàn dámòràn púpò tàbí gba ènìyàn nímòràn nípa ohunkóhùn tí ba se ènìyàn. Idí nìyí tí wón fi ń pé wón ní ilé ìbágbé.
20231101.yo_2129_39
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A0d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%ACl%C3%BA%20M%E1%BB%8Dd%C3%A1k%E1%BA%B9%CC%81k%E1%BA%B9%CC%81
Àwọn àdúgbò ìlú Mọdákẹ́kẹ́
Ìtumò: Wón ní ní ayé àtijó bàbá kan wà tí ó máa n sòrò tí yó sì yo kòmóòkun òrò tó bá so pèlú, àwon aládùúgbò tí ò tí won máa ń wá kó ìlànà tí ènìyàn fi máa ń ba ènìyàn sòrò tírú eni béè yó sì gbó òrò náà ni àgbóyé. Idi nìyí tí wón fi so ilé máa ní ilé agbédè.
20231101.yo_2129_40
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A0d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%ACl%C3%BA%20M%E1%BB%8Dd%C3%A1k%E1%BA%B9%CC%81k%E1%BA%B9%CC%81
Àwọn àdúgbò ìlú Mọdákẹ́kẹ́
Ìtumò: Wón ní ìdí ti wón fi ń pe àwon ní òkódò ni pé ilé àwon ti omi pé omi yìí gan-an ló sì yí àwon ka pèlú.
20231101.yo_2129_41
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A0d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%ACl%C3%BA%20M%E1%BB%8Dd%C3%A1k%E1%BA%B9%CC%81k%E1%BA%B9%CC%81
Àwọn àdúgbò ìlú Mọdákẹ́kẹ́
Ìtumò: Ìtàn so fún wa pé, nítorí pé àwon tó wà ní agbo ilé yìí féràn láti máa yin olúwa logo ni wón se so wón di agbo ilé ògo.
20231101.yo_2129_42
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A0d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%ACl%C3%BA%20M%E1%BB%8Dd%C3%A1k%E1%BA%B9%CC%81k%E1%BA%B9%CC%81
Àwọn àdúgbò ìlú Mọdákẹ́kẹ́
Ìtumò: Sàngó ni wón so pé àwon tí wón wà nínú ilé yìí máa ń bo láyé àtijó, ibè gan-an ni a lè so pé ojúbo sàngó gan-an wà nígbà náà láti ìgbà tí à ń wí yìí ni wón ti ń pè wón ni agbo ilé baálè Sàngó.
20231101.yo_2129_43
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A0d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%ACl%C3%BA%20M%E1%BB%8Dd%C3%A1k%E1%BA%B9%CC%81k%E1%BA%B9%CC%81
Àwọn àdúgbò ìlú Mọdákẹ́kẹ́
Ìtumò: Wón ní àwon omo tó wà ni agbo ilé yìí burú ju èpè ìdílé lo láyé àtijó tó fi jé pé òkò ni gbogbo àwon omo yìí máa ń lè kiri àdúgbò nígbà náà, èyí ló mú won so orúko agbo ilé won ní agbo ilé òkò.
20231101.yo_2129_44
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A0d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%ACl%C3%BA%20M%E1%BB%8Dd%C3%A1k%E1%BA%B9%CC%81k%E1%BA%B9%CC%81
Àwọn àdúgbò ìlú Mọdákẹ́kẹ́
Ìtumò: Orúkò enìkàn tí ó kókó dé àdúgbò nì wón fi so àdúgbò náà ni orúko rè. Wón ní òun gan-an ni wón fi je alága àdúgbò náà.
20231101.yo_2129_45
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A0d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%ACl%C3%BA%20M%E1%BB%8Dd%C3%A1k%E1%BA%B9%CC%81k%E1%BA%B9%CC%81
Àwọn àdúgbò ìlú Mọdákẹ́kẹ́
Ìtumò: Wón ní eni tí ó bá sè ni àwon ilé yìí máa ń gbé ni gídí gánún lo bá baálè láàfin rè láyé àtijó, won kì í jé kí esè irú enì béè kanlè títí tí won ó fi gbé e dé ibi tí wón bá gbé e lo. Ìdí nìyí tí wón fi ń pe ilé yìí ní agbo ilé ògìdìgànún
20231101.yo_2129_46
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A0d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%ACl%C3%BA%20M%E1%BB%8Dd%C3%A1k%E1%BA%B9%CC%81k%E1%BA%B9%CC%81
Àwọn àdúgbò ìlú Mọdákẹ́kẹ́
Ìtumò: Adúgbò yìí náà dàbí ti okè tí mo kókó menu bà télè, orúko eni tí ó kókó dé àdúgbò yìí ni wón fi so àdúgbò yìí lórúkò tí wón sì ń jé orúko náà di òní olómìí yìí.
20231101.yo_2129_47
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A0d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%ACl%C3%BA%20M%E1%BB%8Dd%C3%A1k%E1%BA%B9%CC%81k%E1%BA%B9%CC%81
Àwọn àdúgbò ìlú Mọdákẹ́kẹ́
Ìtumò: Ìtàn so fún wa pé, wón le nílé béré yìí láyé àtìjó, Ìbèrù yìí ni wón gbìn sókàn àwon ènìyàn láti má jè é kí àwon omodé máa ta félefèle lo sí àdúgbò won láti se ohunkóhun. Ìdí nìyí tí wón fi ń pè wón nílé bérí.
20231101.yo_2129_48
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A0d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%ACl%C3%BA%20M%E1%BB%8Dd%C3%A1k%E1%BA%B9%CC%81k%E1%BA%B9%CC%81
Àwọn àdúgbò ìlú Mọdákẹ́kẹ́
Ìtumò: Ní ayé àtijó, wón ní kò sí irú ojà tí ènìyàn lè gbé dé agbolé yìí tí kò ní rí tà. Ìdí nìyí tí wón fi ń pè é ni ilé òòtà.
20231101.yo_2129_49
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A0d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%ACl%C3%BA%20M%E1%BB%8Dd%C3%A1k%E1%BA%B9%CC%81k%E1%BA%B9%CC%81
Àwọn àdúgbò ìlú Mọdákẹ́kẹ́
Ìtumò: Wón ní ní ayé àtijó, wón ní ilé kan soso tó wà ni àdúgbò yìí pa amò ni wón fi kó ilé náà, fún ìdí èyí tí ènìyàn bá ti ńlo ibè won a ní ilé monde, ilé móńdé. Ìdí nìyí tí wón fi só dilé móńdé.
20231101.yo_2129_50
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A0d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%ACl%C3%BA%20M%E1%BB%8Dd%C3%A1k%E1%BA%B9%CC%81k%E1%BA%B9%CC%81
Àwọn àdúgbò ìlú Mọdákẹ́kẹ́
Ìtumò: Gégé bí a se mò pé sàká gan-an jé Ìtore àánú fún àwon aláìní ènìyàn, èyí lò mú kí àwon ara ile ońsàká sora won ni orúko yìí nítorí pé wón ní bàbá kan wa ní agbolé yìí ni ayé àtijó to máa ń se ìtore àánú fún àwon ènìyàn lopolopo. Bí àwon alámùlégbè won se so won ní agbolé ońsàká nìyen.
20231101.yo_2130_0
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A0d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%ACl%C3%BA%20Il%C3%A9-If%E1%BA%B9%CC%80
Àwọn àdúgbò ìlú Ilé-Ifẹ̀
Ìtumò: Ìwádìí so fún wa wípé nígbà tí òrànmíyàn fé wolè ó so fún àwon àgbà ifè wípé tí won bá tí ní ìsòre kí wón má pé òuni kò pé ní àwon àláìgbàgbó kan bí lope láìsí ìsòrò bí óse fí ìbínú jáde sí wón tí ó sí ńbe wón lórí lo ibè ní àwon àgbègbè bá le pàdé rèní wón bá so fún wípé kó má bínú pé àwon omorè náà ní bí àwon àgbàgbà se so wípé Ìré-lórí-mo Iremo.
20231101.yo_2130_1
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A0d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%ACl%C3%BA%20Il%C3%A9-If%E1%BA%B9%CC%80
Àwọn àdúgbò ìlú Ilé-Ifẹ̀
Ìtumò: Nípa sè erú ní orúko yíi ti je jáde erú kan ti olówó kan ni agbègbè yíi ni óni ogún ni ojó kan wón níkí o gun orí àjà lo láti lo sisé ó gún orí àjà naa ó sì bímo sí ibè osì so wípé láti ojó naa ni aboyún àdúgbò naa yo tí má bímo sí orí àjà àwon tí kò sí tèlé ohun tí ó so omo yìí, omo won ń bèrè sí ń ku.
20231101.yo_2130_2
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A0d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%ACl%C3%BA%20Il%C3%A9-If%E1%BA%B9%CC%80
Àwọn àdúgbò ìlú Ilé-Ifẹ̀
Ìtumò: Ni àdúgbò yíi isu ti ó dára pò ni ibè, ìdí ni wípé wón ńbe ógbin isu ògbìn isu daradara íbè wón sí má ń di isu ní ìdì, bí ìdi ní, ìdi nìyí tí wón se ń pe ni Arùbidì
20231101.yo_2130_3
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A0d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%ACl%C3%BA%20Il%C3%A9-If%E1%BA%B9%CC%80
Àwọn àdúgbò ìlú Ilé-Ifẹ̀
Ìtumò: Ìtàn so wípé àdúgbò yí jé bi tíó jé àlà nígbà tí ifè àti ilésà fé má jà sí ilè wón wá so wípé kí àwon mó jà pé tí ó bá din í òla kí á jí sí ònà kí á pàdé ara sùgbón àwon ilésà kò sùn sùgbón ifè tí sùn ìgbàtí wón má jí ilésà tí dé òdò won, wón wá wò pé Enu owá la ó ma pe àdúgbò yi Enuwa.
20231101.yo_2130_4
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A0d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%ACl%C3%BA%20Il%C3%A9-If%E1%BA%B9%CC%80
Àwọn àdúgbò ìlú Ilé-Ifẹ̀
Ìtumò: Orúko àdúgbò yíi wá nipa sè wípé ó jé Ogbà tí olórun fí Adámù àti Éfà sin i ìsèdálè ayé gégébí ase mò.
20231101.yo_2130_5
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A0d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%ACl%C3%BA%20Il%C3%A9-If%E1%BA%B9%CC%80
Àwọn àdúgbò ìlú Ilé-Ifẹ̀
Ìtumò: Àdúgbò yí jé yo nípa sè ìyá Oba adésojí Adérèmí tó jé àfé kéhìn tí ó má gbá àwon imín àwon eran tí ó má ń wá níta ilé wón òun ní wón wá so dí ajígbáyín