text
stringlengths 9
354
| label
int64 0
1
|
---|---|
RT @user: agbebo adiye to mu adiye iranna lo, e ran leti o pe adiye iranna ki se oun a Je gbe o. | 0 |
RT @user: Yoruba is Sweet. LWKM @user: Aare Orile ede Nijeria Dokita Goodluck Jonathan ko ni lakaye tabi ogbon ... h ... | 0 |
@user òkèlè bàmbà a há ọmọ lọ́fun | 0 |
Tó bá yá, àwọn ẹlẹ́nu èké á ní ìran adúláwò ò lọ́gbọ́n ní poolo orí. Ìbéèrè mi ni pé, báwo ni wọ́n ṣe mọ̀ nípa orín. #LoOrin #Yoruba | 0 |
Tọ̀sán tọ̀sán ní ńpọ́n ìtalẹ̀ lójú; bílẹ̀-ẹ́ bá ṣú yó di olóńjẹ. #EsinOro🐎 #Yoruba | 0 |
Stop attacking me. Meal plan ti forí ṣọ́pọ́n🤦🏾♀️ https://t.co/arNCz1VvPM | 0 |
Egbirin ote. Iwoyi laro ti wan se mo wipe oye ki omo Karo o jire fi owo so wo po. Wan ti ri awon mekunu ge ge bi opon ayo. #YorubaRoNu! https://t.co/PYviiQ267O | 0 |
@user @user @user @user Mo tún taari iṣẹ́-ìjẹ́ mìíràn sí NB, torí ó ń dùn mí wípé wọn kò kà mí kún, nítorí wọn kò rí ẹ̀sùn náà bí ohun tí à ń gbé ní lánkẹ̀. Ohun tí kò tó bàbàrà ni @user kà á sí, ó sì ju bàbàrà lọ. #EtoOnibaara #consumerright #brandnegligence | 0 |
YORUBA CURENTLY UNDER FRINGE ATTACKS BY FULANI MILITIA. #KeepitOn #yoruba #YorubaNationNow #EndNigeriaNowToSaveLives Eyin agbalagba iranu playing greedy politics with the future if yorubaland E ni ku sibi ti aso yin wa. cc @user @user @user https://t.co/4JQHzEhfIe | 0 |
RT @user: Ojo ti iwa jegudu-jera ati Iwa eyii'okanmi ba kase'nle RT @user: Ọjọ́ wo ni ètò ìlera tó péye máa to wà ní #Nig ... | 0 |
@user @user hmm. Ó yẹ́ mi. àmọ́ adé ẹ̀gún dà lóri ààfáà? Bóya kí n darapọ̀ mọ́n wọn kí n máa na ààfáà lẹ́gba lọ :) | 0 |
Afárá kìíní, ìkejì àti ìkẹta tí Erékùṣù Èkó ni ìdíwọ́ wà. Àwọn kan ní kẹ̀kẹ́ alùpùpù ọ̀kadà tí ìjọba f'òfin dè l'ó fa sábàbí 😶 https://t.co/TOglvtL6S7 | 0 |
Magí nìkan l'oúnjẹ ẹlòmíì, bí kò báì da magí lu oúnjẹ, kòì dá'ná. #Kemika | 0 |
RT @user: Dókítà ọ̀mùtí ní India se iṣẹ abẹ tó mú ẹmi olóyún àti ọmọ rẹ̀ https://t.co/Om4RFJ9NPj | 0 |
Irọ́ baba irọ́! Olé, baba olé! Èké baba èké! #Britain #Europe | 0 |
Eléyìí ti sọ àdírẹ́sì nù. Òkúùgbẹ́! #TweetYoruba la pè é, kì í ṣe #TweetIranu https://t.co/ZXd9mQ8a3R | 0 |
15. #PariOweYii Ẹ má wo ti Pẹ̀là, b'ẹ́ẹ bá wo ti Pẹ̀là, ijó yóò bàjẹ́... #Ibeere #Yoruba #Owe | 0 |
Mo ti pè pè pè 111 títí síbẹ̀ kò sí àtúnṣe, gbogbo ohun tí wọ́n ní ń ṣe ni mo ti ṣe. @user @user @user | 0 |
O to eniyan merindilogun(16) ti o ti di ero orun bayii ninu agbara ojo Sandy, eyi ti o sose ni etido ila oorun (East Coast) ni Ile America | 0 |
Onijamba gba ni Aare GEJ @user o i ti fI ase si iplongo ibo beni egbe @user jade won kampeeni kaakiri Nijeria labe asia TAN | 0 |
#Yoruba Abere sonu won lo gbe Sango. Oun ti o sonu yoo ju epe lo. | 0 |
Oro Akpabio yi ma dun yin lopolopo o! Sebi beyin na se gbe gba oti, ti emu ijo jo, beresi polongo lori Twitter nigba ti awon omo egbe oselu APC darapo mo egbe PDP ni yen. https://t.co/D3sjqr1JWw | 0 |
Tobi fe fi Facebook se 419 scam fun awon ara Ilu Oyinbo. O fe scam videographer Adam Grumbo sugbon oju Adam ti la Adam fi Western Union send $100 si Tobi ki o ma ya photo & video Nigeria Adam tun ba si YouTube & GoFundMe🤔🤔 https://t.co/EOCYverlIQ via @user #TweetYoruba https://t.co/98eIx5XMOW | 0 |
@user: What is 'Gbana'?""""@user: Davido a ma se bi eni to fa gbana ninu video...""""""""gba'ná; gba iná = to set ablaze #InYoruba | 0 |
@user bẹ́ẹ̀ ni ẹnìkan tí mo fi orúkọ bò láṣìírí, ṣe jí iṣẹ́ ọpọlọ mi, láì Kansárá sí mi. @user @user | 0 |
Wọ́n pín wa yẹ́bẹyẹ̀bẹ, wọ́n fi orúkọ mìíràn ró wa láṣọ titun. #Nigbatiwonde | 0 |
@user @user @user O le te obirin lorun 😣 #TwitterYoruba | 0 |
...Ẹlẹ́yàmẹ̀yà ò dáa nínú ọ̀rọ̀ òṣèlú rárá, Bá á bá fẹ́ móhun tó dáa bọ̀ níbẹ̀, Èmi kì í ṣe Íbò, Haúsá ni mí, Èétijẹ́ tọ́mo Yorùbá yóò máa ṣèjọba lórí wa? Ẹ jẹ́ á pàyẹn tì, Ìbá dára ká forí ìkookò ṣọ̀ọ́dun..."""" #AsayanEwi #Atelewo #YorubaBooks #Yoruba https://t.co/IlPA4rWzq3 | 0 |
RT @user: """"""""@user: Chile ti ṣílé Spain | #Brazil2014 #idanoripapa"""""""" Oma se o. Se' Spain ni awon Chile wa n ko igi iya fun bayi? | 0 |
Ó ṣe'ni láàánú pé ṣàṣà èèyàn ló ṣì ń lo irú, ògìrì, olú fi se'bẹ̀ láì má fi èròjà èèbó tí a mọ̀ sí MSG síi. #Kemika | 0 |
Àwọn pípù yìí kàn án mú wa nígànán ni. Irúkan náà ni gbogbo wọn. Àti APC, PDP, AIDS, HIV, àrùn kan náà ni. | 0 |
Ṣé nítorí kò gbà fún ọ, lo ṣe fi tipá tipá báa lò pọ̀? #IWD #marchagainstrape | 0 |
Àwọn òfin wọ̀nyí mú kí Òronsẹn di ọ̀tá àwọn ìyáálée rẹ̀, wọ́n ń rẹkẹ rẹ̀ torí kò sí ohun tí wọ́n lè ṣe lójú ọkọ wọn. #Igogo | 0 |
Ọ̀gbẹ́ni Bọ́lájí ní àwọn ò ní fi àyè gba ìwá jẹgúdújẹrá lákàtàa ìṣèlú wọn. #Apero2015 #Yoruba | 0 |
Owó tí à ń sọ nì, ló pàpà wọ inú ilé ìkówópamọ́sí àyà ìyá ẹlẹ́ja l'Óṣòdì. Àṣà kíki owó bọ kọ́mú nígbàogbo kìí ṣe nǹkan tó dáa. #Naira | 0 |
RT @user: Oro awon ara oke-oya yii wa su wa oo,bawo lese maa yinbon fun awon osise ilera bahun!!! | 0 |
Aluwala olongbo, àti kò ẹran je nii #Yoruba https://t.co/ax2vykzwLl | 0 |
12. #PariOweYii Ẹni t'ó sọ ilé nù... #Ibeere #Yoruba #Owe | 0 |
.@user kini gbo gbo serenren yi, ema lo si ile ki elo ma je eba ko lobe. @user ma pe yin ti o ba kan yin. https://t.co/S4YQpXCp6Y | 0 |
Ẹní fẹ́ arẹwà, ó fẹ́ ìyọnu #owe #Yoruba | 0 |
Odò ló bàa jẹ́ https://t.co/jdDvX4u2l8 | 0 |
Bó bá ti ẹ̀ jẹ́ pé bí a bá lo ìpara, ọṣẹ àti àwọn èròjà ìpara tán ara á gúnrégé, àmọ́ kọ̀ rí bẹ́ẹ̀ rárá #arabibo #omoyoruba | 0 |
Bí o kò bá ní ìgbàgbọ́ nínú ara rẹ, báwo ni ẹlòmíì ṣe máa nígbàgbọ́ nínú rẹ?"""" - Deion Sanders #TranslatedQuotes #AnyQuoteInYoruba #RandomQuotes #RandomThoughts #Quotes #YorubaTranslator #IyaYoruba https://t.co/89D8ClwqSt | 0 |
Eniyan ti o so le nu o so apo Iya Ko. Da n saki fun ede ati asa yoruba. #TweetinYoruba | 0 |
fòyà. Nítorí akọni àti akíkanjú ọkùnrin ni òhun fúnra rẹ̀ jẹ́. Àwọn ọmọ ogun bá fi ipá wọ inú ààfin. Aláàfin Káràán dúró bá wọn taá tán. Ó bẹ̀rẹ̀ si ní fi ọfà jà, tí ó ń yin ọfà pa àwọn ọlọ́tẹ̀ náà. Ó ta ọfà títí, ọwọ́ rẹ̀ wú. Nígbà tí ìjà náà gbomi, ó gun | 0 |
2.Òwe àlàyé ni """"""""pàṣán tí a fi na ìyáálé, ń bẹ lájà fún ìyàwó"""""""", Pa òwe alálàyé mìíràn. #ibeere #Yoruba #Owe | 0 |
Yorùbá ló gbé àṣẹ lé ẹ̀yà ìyókù lọ́wọ́, ní báyìí ìran Yorùbá ó lẹ́nu ńbẹ̀ lọ títí, wọ́n ń pàṣẹ fún wa ní sáà tí a wà yìí ni. #IjoOle | 0 |
RT @user: """"""""@user: Wọ́n ni alàgbà Ṣagari náà rí jẹ níbẹ̀. Àgbààyà bàbá. #DasukiGate"""""""" baba o sa jeun, abi? | 0 |
Àwọn àmi bi ẹ̀fọrí, araríro, òtútù, rírẹni àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ. #malaria #WorldMalariaDay #yoruba #RollBackMalaria | 0 |
Ohun àbùkù ni fún ọ̀dọ́mọdé, láti na ọwọ́ sí àgbàlagbà, fún ìkíni. Èyí tí ó tako ìlànà ìtẹríba tàbí ìdọ̀bálẹ̀/ìkúnlẹ̀, ní ilẹ̀ Yorùbá | 0 |
RT @user: @user :Oga o,o is dun ni gidigidi. | 0 |
RT @user: Ogun ayé ò ni ìgbà ìsimi, ogun ayé ò ni ibòji, o d’ijọ́ a bá dé ‘bojì. #OgunLaye #YorubaPoem #Yoruba | 0 |
Ó dà bíi wípé àwọn ọmọo wa ńta bíọ́bíọ́, pẹ̀lú ariwo yìí #nigeria | 0 |
Gbogbo àwọn òòṣà wa ń sunkún..."""" Ojú ìwé 182, orí 24, Ìgbésí Ayé Okonkwo #ThingsFallApart #Yoruba #chinuaachebe @user https://t.co/z1DKJN5sPl | 0 |
RT @user: Ìbàjẹ́ ọjọ́ kan kì í tán lógún ọdún. / An indiscretion of one day, does not get forgotten in twenty years. [Acting in … | 0 |
@user @user Ọbẹ̀ awun l'ó pa awun. #FreeWale https://t.co/9w5yvqTMVl | 0 |
Bi ewure Eni ba sa wo ile alagidi, bi eyan o ba pada lenu ona, iya to ye ko je ewure nio pada wa jeni #yoruba #proverb (I don't really know how to translate in english) buts it summarises as, one has to be smart before confronting issues, so one does not regret it | 0 |
Awuyewuye àwọn èdè tó fẹ́ parẹ́ yìí mà ń ta mi lára kẹ̀ẹ. #YorubaONiParun | 0 |
Ẹni ija o ba lon pe ara ẹ l'ọkunrin. Translation: He who haven't seen real fight/battle boast of being a SuperMan. ~@user #kevingatesvideo #yoruba #language #RemiCrownDiamond #sundayvibes #SundayMotivation | 0 |
Aja toma sonu, kin gboo fere olode.... | 0 |
Omo @user Sade fe ki @user so ijoba Nijeria di OyeIdile, O fariga pe @user o pin ipo kan Iya oloja https://t.co/dnLtCg0uCo | 0 |
Ẹ tiẹ̀ gbọ́ ná, iwin ni #Shekau ni àbí ènìyàn ẹlẹ́ran-ara bí i tiwa? Ó ṣe wá di eku ẹmọ́ tó ń bọ́'rù mọ́n àwọn ọlọ́gun wa lọ́wọ́? #BokoHaram | 0 |
RT @user: Ole ni gbogbo awon oloselu wa patapata """"""""@user: Gbèsè orílẹ̀ tó kù díẹ̀ ká san tán l'áíyé Ọbásanjọ́ ni wọ́n ti tún ... | 0 |
RT @user: @user @user @user @user ohun to seni laanu ni wipe awa funra wa ko mo nipa ohun to je… | 0 |
- Jẹbẹtẹ gbọ́mọ lé Sanwóolú lọ́wọ́ : Inúu Sanwóolú bàjẹ́ - Ìdí 'Láperí domi nígbà tí ó gbúròó ìbọn : Ẹ̀rú ba 'Láperí nígbà tí ó gbúròó ìbọn #AkanloEde #Yoruba https://t.co/Nowv6dkRaW | 0 |
.@user were yin ti wa woja o! se asofin ipinle @user Afolabi Akanni ti ekigbe wipe DSS pa ko yi? https://t.co/p3wDPcXJ6I | 0 |
Ṣé o rántí wípé arábìnrin #Rice láti #America ni a gbọ́ pé ó fún Ọláwálé ní kíni kan bíi àgbo mu ni baba bá dákẹ́? #June12 #Abiola | 0 |
RT @user: T'oró t'oró l'ejò ńrìn; ejò ò ní padà lọ mú oró wá ní'lé. / Snakes slither around with their venoms; they'll never go… | 0 |
RT @user: Òkóbó ò le è fi alátọ́sín șẹ̀sín. Òwe míì fún ọ̀ràn Ọọ̀ni àti Elékòó. #Yoruba #Oduduwa | 0 |
RT @user: Congo Ti Le Eye Asa Nigeria Loko Pa: Orileede Congo ja irawo Super Eagles lana Satide (6-9-14) ninu okan lara ... http://t.co/0… | 0 |
... Tii Koo Baa Nii Idi ... Alapinni Koo Gbodo Gba Alagbaa Nii Eti ... #Yoruba. #OKAY. | 0 |
RT @user: @user òun nìkan kọ́ ni ẹ̀sùn yìí kàn o, ṣàṣà nínúu wọn lọmọ wọn ńbẹ̀ lókè òkun ìsàlẹ̀ ọ̀sà. Ni ọ̀rọ̀ ìlú yìí ò f… | 0 |
RT @user: Awon kan ma fi lulu ni oju titi,ariwo yen ko da rara RT @user: @user @user Bẹ́ẹ̀ ni. Ariwo ti pọ̀jù. | 0 |
@user Ori yin o pe sir #2019in5words | 0 |
#iroyin, #yoruba, Okanjua re o! Mose si mu ogogoro ku nitori egberun merin naira: Omokunrin… https://t.co/vZTwUApUVL | 0 |
...ìwo àti gbogbo ènìyàn lo ni ètó láti gbé ìlé àyé. O si lòdì sí òfin láti kpa ènìkéni. #Law2go #HumanRightsinNigeria #section33 #yoruba | 0 |
Breaking!!! Senator Ajumobi is dead!! Oda bo. RIP Details later #ogunupdate #Yoruba #odudua https://t.co/8mV8HTeSQi | 0 |
Abi ile aye yi kọ? Abi ile aye yi kọ? Mo ni Abi ile aye yi kọ? D’ijú, kí o se bi ẹni kú, ki o ri bi aye se fẹ ọ tó #YorubaPoem #Yoruba | 0 |
Ìṣẹ̀lẹ̀ tí ó bá ṣẹlẹ̀ sí ẹja nínú ìṣasùn, ìwọ̀ l'ó kó o bá a. #EsinOro🐎 #Yoruba | 0 |
Àlàyé bí Ọlọ́run Olódùmarè ṣe dá ayé gẹ́gẹ́ bí ọjà tí ọmọ aráyé wá ná ni ẹsẹ̀ Ifá yìí ń sọ fún wa. Wọ́n sì lá ò mọ Ọlọ́run. #YorubaMoOlorun | 0 |
RT @user: Ewu ńlá ńbẹ nínú epo-rọ̀bì! http://t.co/W4I7qYaJ | 0 |
Ẹrú kú nílé, wọ́n lọ sin ín s'óko. Ọmọ kú lóko, wọ́n lọ sin ín sílé. Bẹ́ẹ̀ nìbí ò jù 'bí, bí a ṣe bẹ́rú la ṣe bọ́mọ. #IworiOkanran #Yoruba | 0 |
RT @user: @user T'oró t'oró l'ejò ńrìn; ejò ò ní padà lọ mú oró wá ní'lé. / Snakes slither around with their venoms; they'… | 0 |
RT @user: Ti wan ba jeun yo tan. Wan ma wa bekun bekun kiri @user: Ọlọ́run ò ní ká má jẹun. Ìjẹ wọ̀bìà ni Ọlọ́run ò fọwọ́sí | 0 |
RT @user: Oniregbe, olojukokoro""""""""@user: Lára ìṣekúṣe lati mú oníṣekúṣe, ẹlẹ́yà ni a ti rí ẹlẹ́lẹ́yà. Ọ̀rọ̀ wo la yọ láti ara ìr… | 0 |
Ta ló rántí orin yìí: ♪ Ọmọ tó mọ́ ìyá rẹ̀ lójú o, òṣì yó ... ♪ ♥ http://t.co/oVBeaaM0mu ♥ #HappyMothersDay | 0 |
Paga ati rogo ni Ile Yoruba! GEJ @user @user ati @user ti ran olopa apanimayoda Mbu si ile Yoruba o http://t.co/XeSOe08zDw | 0 |
Kò ṣẹlẹ̀ rí, kò ṣẹlẹ̀ rí, ọjọ́ kan náà ni yó ṣẹlẹ̀. Àìsí ináa mànàmáná fún àìmọye ọjọ́ ni ti wa ń bí. ⚡ https://t.co/EFRnrHU5pg | 0 |
Ti e ba gbe ina kari,e ba ekun mi ni buba. #TweetinYoruba | 0 |
Amúnibúni ẹran Ìbíyẹmí; Ìbíyẹmí fọ́jú, ẹran rẹ̀ náà dití. Yorùbá ń gbáyé lọ, àwọn àpọ̀dà ò já. Ẹ ṣá máa wò mí. 😀 | 0 |
#IrohinYoruba Bii ile aadota ni o jona guguru nigba ti Hurricane Sandy kolu ile-ise ipese ina oba kan, ti iyen si gbina #yorubanews | 0 |
Ko ma ragba fun English. #yoruba legit❤️ https://t.co/lYI7t4SIPy | 0 |
Eṣinṣin tí kò bá gbọ́ ìkìlọ̀ ló ńbá ọ̀gẹ̀dẹ̀ wọ ẹnu ọ̀bọ. / Only a disobedient housefly accompanies (a bite of) banana into the monkey's mouth. [Moderation is it; lack of self-control can be costly.] #Yoruba #proverb | 0 |
Ìjọba ìgbàlódé ti fi ọjọ́ pípẹ́ ba àṣà ìbílẹ̀ jẹ́, wọ́n ti fi ìṣẹ̀ṣe ṣe yẹ̀yẹ́, wọn kò fẹ́ ìlọsíwájú nǹkan ìbílẹ̀. Ọ̀ràn orísìírísìí ni àjọ ọba òde òní ń dá, ẹ wo pálapàla ti Ìwó nípìínlẹ̀ Ọ̀ṣun tí ó ṣẹlẹ̀. #OosaNiObaIleYoruba #Isese #Yoruba | 0 |
Ẹ wo gbogbo èso tí kì í fi bẹ́ẹ̀ tóbi tí ó kún 'ta bí wọ́n ṣe tóbi gbẹ̀ngbẹ̀, aàrùn ló ń fà ságọ̀ọ́ ara. Ikún ń jọ̀gẹ̀dẹ̀... #AyajoOjoIle | 0 |
Kí ni ò gbówó lérí, afẹ́fẹ́ ìdáná ò ṣe é rà, epo parafín àti bẹntiróò ò ṣe é kàn, kò sì yọ irun kan lára yín. @user #IjoOle | 0 |
#JoyousMoment oga o, ijeta ko ni Minister Ochoji ku pelu awon molebi e, sebi Tira ni won ni iwo @user ka? https://t.co/5QieVzGvPp | 0 |
... tíwà ìbájẹ́ ọ̀hún ti dé góngó, aráàlú ò sì le è gbà á mọ́, ó ní ohun tí wọ́n yóò ṣe. #Kirikiri #Yoruba #IseleAtijo | 0 |
@user @user @user Fúlàní tún pààyàn lábúlé Babaláwo/Kájọla, ìjọba ìbílẹ̀ Ewékorò, Ìpínlẹ̀ Ògùn. Wọ́n ṣá olùkọ́bìnrin náà pa. @user @user @user | 0 |
RT @user: Airin jinna lai ri abuke okere,... __RT""""""""@user: Ẹ gbàmí! Ẹja tútù ni àwọn wọ̀nyí ń kó jẹ bí ẹní jẹ̀bà o. http://t.c… | 0 |