text
stringlengths 9
354
| label
int64 0
1
|
---|---|
Ó tìtorì OGÚN (Inheritance) dá OGUN (war) sile. OGUN (war) dé O n la ÒÓGÙN.(sweat) Ó lo sí ÒGÙN (state) lo gba ÒÒGÙN (medicine) lódò ÒGÚN (god of iron) OGÚN (twenty) ojo lo fi lo ÒÒGÙN (medicine) ÒÓGÙN(sweat) Isn't this beautiful? #yoruba #ONDO | 0 |
Igbó biribiri; òkùnkùn birimù birimù... @user https://t.co/rXNrso2CLL | 0 |
Ancestors in trouble. Nigerian Army need some slap for all the abuse. . . 👉 Yorùbátv ẸGBẸ ỌMỌ OLÚWA BÍ GBOGBO ÀGBÁYÉ Ojú òpó ìkànsíraẹni 🇳🇬🇹🇬🇧🇯🇧🇷🇨🇴🇨🇺🇬🇭🇨🇮______________________________□ Yoruba TV 🥰😘🔥 #yoruba #yorubatv… https://t.co/7FXtX8TKCu | 0 |
RT @user: @user Been, won ti so omoluwabi won danu si'gbo. | 0 |
Ọbáléndé Suya ni mo ti jẹun ọ̀sán lánàá. Ó ti pẹ́ tí mo ti lọ síbẹ̀ gbẹ̀hìn. Kò dà bíi ti tẹ́lẹ̀ mọ́. #Obalende #Suya #Peckham | 0 |
Ó ṣeni láàánú pé àwọn ọmọ ìyá mi ò mọ ira wọ́n mọ́, wọ́n fẹ́ máa ṣe bí èèbó ní gbogbo ọ̀nà. #YorubaRoNu | 0 |
A kì í ní ọba méjì nílùú kan, Àfọ̀njá gbéná karí, ìbànújẹ́ gba ọkàn-an rẹ̀ po nítorí ó pàdánù òye Aláàfin, ó di ọ̀tá ọba. #Darandaran | 0 |
Àwé, jẹ́ k'ọ́ mọ̀ wípé ìjàmbá ọkọ̀ dánfó ló fa súnkẹrẹ fàkẹrẹ ní kété tí a bá kúrò ní Adéníji, bí a bá ń lọ Òwòrò. #3RDMB @user 🚌 | 0 |
@user: Tattoo Lati Inu Orun Apaadi?: Sebi ti oge ba po lapoju ... http://t.co/x2WuaXA6fc"""" Ilà ńkọ́ o? Ṣé kì í ṣe lati ọ̀run àpáàdì? :) | 0 |
Bìlísì yóò wà nínú ìdè fún ọgbọ́n ọjọ́, lẹ́yìn ọgbọ́n ọjọ́ wá ńkọ́? Bìlísì á gba òmìnira. #OroSunnunkun #Yoruba | 0 |
Ó ṣeni láàánú pé ọ̀pọ̀ ọ̀mọ̀wé 'ò ṣe iṣẹ́ ìwádìí ti wọn láti yẹ ìtàn èèbó wò, gbogbo ohun wọ́n kà ni wọ́n gbà. #Yoruba | 0 |
RT @user: """"""""@user @user : Igbakeji Are ana; Atiku ko iwe si egbe Oloburela lori ai kopa re to ni nu egbe. http://… | 0 |
Jeki ori e pe ooo ,Ma fo ori e danu nisi 🤣🤣🤣 #9ja #yoruba https://t.co/Ja7wnahOWD | 0 |
Àwọn gómìnà ń ṣe ìgbéyàwó fọ́mọ wọn nígbà tí Boko Haram ń ko àwa lọmọ lọ"""" Olóòtú Sahara Reporters tí fọgba yángan https://t.co/PKnjtThIZ6 https://t.co/Nl5Ssd9tws @user @user #Yoruba #OlayemiOniroyin | 0 |
... Ẹ̀yin ni ẹ sọ wípé tí ọmọdé bá kú, ẹ ní wọ́n á wá owó sin ín Ẹ ní tí àgbàlagbà bá kú, ẹ ní wọ́n á wá owó sin ín Ti omijé ti ẹ̀jẹ̀ ni wọ́n ń fi í wá owó òkú... | 0 |
Àmọ́ lẹ́yìn ọgọ́rùn-ún ọdún, Ènìyàn dúdú kò ì tíì ní òmìnira. Ọgọ́rùn-ún ọdún tẹ̀lée, ó dun 'ni, ìgbé-ayé Ènìyàn dúdú ṣì wà nínú ìdè ìpínyà tòun elẹ́yàmẹyà. Ọgọ́rùn-ún ọdún tẹ̀lée, àwọn Ènìyàn dúdú ń dá gbé lóríi erékùṣù ìṣẹ́ àti òṣì láàárín gbèdéke aásìkí. | 0 |
ọ̀pàpà paradà ó dèèmọ̀ gòdògbò taani ò mọ̀ pẹ́nu àgbà òṣèlú lèèmọ̀ ti ń gbó àgbà òṣèlú, àgbà ọ̀jẹ̀lú https://t.co/3GDAByaS6r #Atelewo #YorubaLiterature #Yoruba #politicians | 0 |
Èéṣe tí ẹ fi fẹ́ fagilé tiwa n tiwa? Ṣé ògidì ọtí ògógóró ní í pa wọ́n ní #Ondo àbí ayédèrú? #Ogogoro #Yoruba | 0 |
Bákan náà, ni ó túmọ̀ sí wípé àrugisẹ́gi tó bá ṣẹ́gi, orí ara rẹ̀ ni yó fi gbé e. #owe #yoruba #owoogede #yobamoodua | 0 |
RT @user: Yorùbá Word of the day """"""""Ìbínú"""""""" ⠀ ⠀ #learnyoruba #yorubawords #AngerinYoruba #ìbínú #nigerianlanguage #yorubalessons #yor… | 0 |
@user, ẹ dá @user sílẹ̀, ẹ kìlọ̀ fún àwọn Fúlàní, kí wọ́n t'ọwọ́ ọmọ wọn baṣọ, wọ́n ń fara ni ọmọ Nàìjíríà. @user @user #FreeAudu | 0 |
Irun dúdú bọ̀lọ̀jọ̀, tó dàbíi òwú niruun wa, màdàrú ni wọ́n ṣe nígbà tí wọ́n ṣe ṣe ṣe kí a gbàgbé ti wa #AwaLaNiIrun | 0 |
Alàgbà ni mí kìí ṣe Ogbeni"""" Yemi Akinwonmi Igbakeji alaga àpapọ̀ fún Gúúsù nínú ẹgbẹ́ òṣèlú @user lo fariga fun @user @user https://t.co/mq432kA3Cw | 0 |
Nitori ibo 2015: PDP koju ija repete si egbe APC http://t.co/EvZkoSCwi5 | 0 |
@user Ṣé ntorí ìrẹsì tóo gbé fún mi"""""""" hahaha. Ṣàngbà fọ́! Ọlọ́run Ọba ò! :) #erinkeekee | 0 |
RT @user: """"""""Bí ìlù bá dún àdúnjù, yóó fàya"""""""". Translation: """"""""If a drum makes too much noise, it breaks"""""""". Lesson: Disaster follows exc… | 0 |
Wọ́n ní ó fẹ́ẹ̀ẹ́ tó ènìà 300 tó ti ṣekú pa. Àìmọye ẹgbẹ̀rún ni wọ́n ti pàdánù ilé wọn. #Bopha #Philippines | 0 |
RT @user: Yunfa ló gba àwọn ọ̀darànmọràn Fúlàní lálejò lókè Ọya, #AareOnaKakanfo Àfọ̀njá ló pè wọ́n wá sí ilẹ̀ káàárọ̀-o-ò-jí-ire. Àm… | 0 |
@user Ìmànle a ti á jẹ́? A à mà ti pè wọ́n báun mọ́ o :) Mùsùlùmí ni wọ́n jẹ́. Toò, ìbéèrè yí ṣe bákan o arábìnrin wa. :) | 0 |
RT @user: Haruna Ishola, baba gani agba wipe; Awon odale ti gun igi rekorja ewe. https://t.co/ErIyblnKQd | 0 |
Adìẹ funfun ò mọ'rarẹ̀ lágbà. #NigeriaAt52 | 0 |
Abule wo ni Lai Mohammed ti wa gan, sebi awon ara Ilorin gbon die, isokuso wo ni agbenuso ijoba Lai nso nipa oro aje https://t.co/GUR3Hx3jNT | 0 |
RT @user: """"""""Ìyà mẹ́ta: O ò ní ìwà, o ò rẹwà, o ò tún lówó lọ́wọ́, ṣùgbọ́n o ní ìgbéraga!"""""""" - #Olahakeemola |#EdeYorubaDunLeti What… | 0 |
A kàn ń gbọ́ ẹni yìí kó mílíọ̀nù sílẹ̀, tọ̀hún gbé bílíọ̀nù kalẹ̀, pẹ̀lú 'ẹ̀, a ò r' ẹ́jẹ̀ a ò r'ómi ra. Wọ́n sé wa mọ́lé, a kò rí ìnawọ́sí ó kéré ó pọ̀ láti ọ̀dọ̀ ìjọba, àwọn tí wọ́n jẹ́ akúṣẹ̀ẹ́ tí wọ́n ní yóò rí oúnjẹ táṣẹ́rẹ́ gbà kò rí. | 0 |
Kò yẹ ó rí bẹ́ẹ̀ rárá. Ìtìjú ńlá gbáà ni ★ It shouldn't be so at all. Its a big shame #YesVernacular #Speak #Write #Read #Yoruba | 0 |
Irọ́ ńlá ni wọ́n pa, kí ti wa máà ba nìyí ni wọ́n fi ní èdè wa ò dára tó, ni wọ́n fi ní kí a jáwọ́ lápọ̀n tó ń yọ. #EdeAbinibi #IMLD17 | 0 |
@user ;) òun rèé o. Tí ẹ bá máa fi Yorùbá ṣe yẹ̀yẹ́, ẹ jẹ́ kó dájú pé Gẹ̀ẹ́sì yín gún régé :) http://t.co/LC6k88h8 | 0 |
.@user ede ko janduku @user ati ogboju ole @user sita bi omo ijo meta #EKITIGATE http://t.co/Catd5fLtwq @user | 0 |
RT @user: @user A le pin ya rara. Ipinya ko ni isoro wa. Awa eniyan ni isoro ara wa. | 0 |
Ọ̀pọ̀ ní ẹnì kan tí ò sí nínú ikọ̀ọ wa fún #worldcup yóò fa ìfàsẹ́yìn fún wa. Ṣé òtítọ́ lèyí? @user #Idanoripapa http://t.co/TRQ4vtw1ZL | 0 |
RT @user: @user @user Èrín àrin t'àkìtì... òrò burúkú t'òun t'èrín...Jonathan gba sátidé lówó re ó gbé sunday le lówó | 0 |
Bí a bá dáṣọ f'ọ́lẹ, níṣe là ń pa á láró. #EsinOro #Yoruba https://t.co/GHfq09vt0k | 0 |
♫♪♪♪ ... ìlẹ̀kẹ̀ ti já báyìí o! Alhaji tí bínú tú láwàní o. Tọ̀ọ̀ ... ♫♪♪♪ @user | 0 |
Ẹ tún fẹ́ gbé wa mọ́ra àbí? Ẹ ti pawó sápò yín tán àbí bẹ́ẹ̀ kọ́? #Nigeria @user | 0 |
Kí l'ó fa ìwà jẹgúdújẹrá, ìjẹ àwòdì jẹun èpè sanra tí ó ti fẹ́rẹ̀ fa ìlú wa ya pẹ́rẹpẹ̀rẹ? #OminiraNigeria | 0 |
Ó ní òun àt'ọkọ-àfẹ́sọ́nà òun láwọn jọ ńlọ, àmọ́ òun kò rọ́kọ òun, òun mọ ibi tó sa gbà, ẹ̀rọ-ìbánisọ̀rọ̀ sì wá ń'nú àpò tí wọ́n gbà #Oshodi | 0 |
Awon olote! Omo Aare Nijeria atijo Dokita Jonatanu oku o! Ebele wa ni America to ohun fi owo Nijeria se yotomi. Ema fi enu pa omo fun olomo | 0 |
RT @user: Ni ile ayé ti ọmọ iya meji ti n p’ara wọn nitori ogún. #OgunLaye #YorubaPoem #Yoruba | 0 |
Àwọn obìin mìíìn ẹ̀wẹ̀wẹ̀ ò ti ẹ̀ ní ọmú àmútọ̀runwá mọ́, ọmú oníke ni wọ́n ń gbé kiri. Irúu wọn ò ní le è fọ́mọ lọ́yàn. Òṣì ò da ńlé pákó. | 0 |
🐝 kùn ún yùnbùnyùnbùn {oyin/agbọ́n/ẹ̀fọ́n kun ọmọ náà yùnbùnyùnbùn\yùnbùn} 🐜 bò ó ṣíbáṣíbá {èèrá bo ìtọ̀ ọ̀mùtí ṣíbáṣíbá/ṣíbá} 🐍 ṣán an ṣókí {ejó ṣán àgbẹ̀ ṣókí} ................ #learnyoruba #Yoruba #language #InYoruba | 0 |
Mo gbọ́ wípé olè wọ ilé ẹnìkan, ó sì kó o lẹ́rù lọ, ni mo bá rántíi """"""""ọ̀wọ̀"""""""" àwọn baba ńlá wa. #OwoFunOle #Yoruba #YorubaScience | 0 |
RT @user: @user #yoruba tok say iku enu atiku Loma npa still😈 omugo agba. | 0 |
RT @user: @user nigbati igbin won ba ti fi enu kan iyo. Kiku loye koku | 0 |
Agbere wu inaki, aasa wu obo, bi won ti n se nile aye naa wu ara orun #Yoruba #funnysayings | 0 |
@user Mo sín in yín jẹ ni. Ẹ̀yin eléèbó ì í kú 'lé. | 0 |
@user ẹ kú sànmánì yìí o. Ṣé nítorí owó Lekki tí kò wọlé! Èbù ìkà tí ẹ gbìn, ọmọ yín, ọmọmọ yín, ìrandíran yín á jẹ ńbẹ. Ó ńṣe ọmọ olókùú bẹ́ẹ̀; wọn ò ní sin ín pẹ̀lú òkú 'ẹ̀. @user @user @user #EndSARS | 0 |
Afọ̀fungbému @user ìsọkúsọ, ọ̀rọ̀ arìnyà lẹ sọ lálẹ́ yìí. Wàláhì tàlahì ẹ máa bá ẹrù yín níbodè, Ọ̀bẹ́lẹ́kún sunkún 'Láaróyè á báwọn ọmọ tí ìyá wọ́n ru oyún wọn f'óṣù mẹ́sàn-án, tí òbí rè wọ́n títí tí wọ́n fi t'ójú bọ́ tí ẹ rán níṣẹ́ sun ẹ̀jẹ̀. | 0 |
L'ana, ọjọ́ Ìṣẹgun, ènìyàn tó ní àrun #coronavirus ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà jẹ́ igba ati m'ọkan-le-l'ọgorin, àjọ NCDC lo sọ bẹẹ. |#EdeYorubaDunLeti #Yoruba #wednesdaythought #CoronaVaccine #COVID19 #COVID #COVID19Nigeria Trump https://t.co/994ep4JoZM | 0 |
Ihoho la ka ra wa ni gba ti moimoi n shoge lol. For Yorubas only🤪 #yoruba #SundayThoughts | 0 |
Ààbà ni a fi ń de ẹsẹ̀ ènìyàn mọ́lẹ̀. Ààbà dà bíi mámu-gaàrí ọlọ́pàá àmọ́ a máa ń fi de ènìyàn mọ́lẹ̀ sí ojú kan ni. Ṣẹ́kẹ́ṣẹkẹ kò yàtọ̀ sí ẹ̀wọ̀n ⛓️tí a fi ń dé ènìyàn níbikíbi ní ara. #Yoruba #Sekeseke #Aaba https://t.co/vFSpmrbCYG | 0 |
... Ẹ bò'díi yín o, ó ti sú wa á wò"""" ►► http://t.co/hUVQWrOcNi | 0 |
RT @user: Ẹni tó yá ẹgbẹ̀fà, tí ò san án, bẹ́ igi dí ọ̀nà egbèje ni. / Whoever borrowed a small sum, but refused to repay it, h… | 0 |
3. #Parioweyii Olè ní í mọ ìpasẹ̀ olè... #Ibeere #Yoruba #owe | 0 |
Àṣà ilẹ̀ òkèèrè ti a gbà lágbá tán, t'ó mú wa gbàgbé ti wa l'ó ń ṣ'okùnfa ìjìyà, àìnílọsíwájú orílẹ̀-èdè wa. #OminiraNigeria #Yoruba | 0 |
Ní sáà tí a wà yìí, àwọn ọdẹ ìgbèríko ti ń ráhùn wípé àwọn kò fi bẹ́ẹ̀ rí ẹran pa nígbẹ̀ẹ́ mọ́ bíi ti àtijọ́. Kò sì sí ohun tí ó fà á bíkòṣe ti ìgbẹ́ tí a ti ń ṣọ gbogbo rẹ̀ di ìletò, a ti pa ìgbẹ́ títí, ẹran igbó ti sá lọ sónà réré lọ ba sí. #EranIgbe | 0 |
Awon ajagun ta! @user ti sa'se, sa'se lai foju kan'run...... https://t.co/FeEwcVh9bu | 0 |
Òyìnbó fi wá sílẹ̀, a ò fi wọ́n sílẹ̀, gbogbo àlàálẹ̀ ìgbà yẹn, náà la ṣì ń bá yí, ikúu rẹ̀ là ń kú lọ. #OminiraNigeria #NigeriaAt56 | 0 |
Ẹran ń kú láì r'ọ́bẹ. #EsinOro🐎 #Yoruba | 0 |
Ǹjẹ́ ìwọ mọ̀ wípé awuyewuye àròyé ọ̀tẹ̀ bẹ́ sílẹ̀ nígbà tí a pa Ajamï (àdàlù èdè Lárúbáwá) tì, tí a bẹ̀rẹ̀ sí í kọ èdè Yorùbá ní ìlànà álífábẹ́ẹ̀tì Rome ní 1875? #Yoruba #orthography #CMS #Roman https://t.co/hPn8P5PdwG | 0 |
.@user ema binu o, lori oro #NigeriaDecides2019 eba wa so fun Alaga eto idibo Omowe Yakubu pe wan ponu. Oku di e ka to. https://t.co/tl54lvA3EU | 0 |
Mo gbọ́ 'polówó tí @user ń tako ìjọba @user pé ó lé #okada, ó gbowó-orí, pé wọ́n kàn án pariwo """"""""ṣangi"""""""" """"""""change"""""""" ni. #Nigeria | 0 |
@user Ohun t'ó bá jọhun, k'á fi we'ra wọn, èpo ẹ̀pá jọ pósí, èlírí jọ imí alábahùn. Èpe l'ọ̀rọ̀ àwọn ará ibí gbà. | 0 |
Aare @user esikis Sir, ema binu o, se wan se ogun MAGBELE fun yin ni? Etun ti kori si ono Equatorial Guinea abi? https://t.co/8AFbLnCXnz | 0 |
Àwọn aláìmọ̀dàbídàbí ní a kì í bá Olódùmarè ní gbólóhùn kí #Islam àti #Christianity t'ó ó là wá l'ójú. #Yoruba #AsaIwure | 0 |
RT @user: Tobi fe fi Facebook se 419 scam fun awon ara Ilu Oyinbo. O fe scam videographer Adam Grumbo sugbon oju Adam ti la Adam fi Wes… | 0 |
RT @user: Oma se o, #abiyamo """"""""@user: Ọ̀fọ̀ ńlá ni k'óòbí ó pàdánù ọmọ. Àt'ìgbà tí 'Júníọ̀' ti kú, ìyáa Júníọ̀ 'ò jẹ́ ará ay… | 0 |
Ilẹ̀ Ìbínú - land of anger. Ìbínú ► Ìbíní ► Benin #etymology #origin #yoruba #yobamoodua | 0 |
Oro olori North Korea dabi omo kekere to ri ibon he, to fi pa eku leekan to wa ro wipe gbogbo nkan ti ohun ba ti ri ni oun le maa koju e si | 0 |
Àti pé, àwọn àbájáde ìwà ìkà tí Europe ṣe ilẹ̀ adú t'ó ń da ọpọlọ adú láàmú dọ̀la ńkọ́, ó yẹ kí a yẹ̀ ẹ́ wò. #OIANUK #BlackHistoryMonthUK | 0 |
RT @user: Yorùbá Proverb: """"""""Ẹni ọgbọ́n pa ò tó nǹkan, ẹni àìgbọ́n pa ló pọ̀"""""""".⠀ ⠀ Translation: Wisdom kills a few, ignorance kills m… | 0 |
Elòmíràn ò ti ẹ̀ mọ òwe kan bèlèǹtàṣé mọ̀ bóyá ó pé tàbí àṣìpa òwe wà. | 0 |
@user: @user eniti kogbon, ni awe n go....awon onijibiti gbogbo!"""" àwọn wo nìyẹn o! | 0 |
Bí a bá tú u palẹ̀ yẹ́bẹ́yẹ́bẹ́, ìséra; ìjánu ìwà àìtọ́; tàbí bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ. Ẹ̀wẹ̀wẹ̀, bí ènìyàn ò bá lè ṣe bí ó ti máa ń ṣe, wọ́n ní ó ti f'ara gbàrùwẹ̀. #Aawe #Yoruba | 0 |
Ó ti tẹ baba fún'gbà díẹ̀ @user | 0 |
Jonathan àti TAN, ẹ kú iṣẹ́ o. Ọlọ́hun ló mọ númbà ilée gbogbo yín o #Nigeria | 0 |
Aṣẹ́wó = prostitute. Aṣẹ́wó = money changer. Aṣẹ́ńwo = ram/cow/goat with broken horn (aṣẹ́-ní-ìwo; ó ńṣòṣì bí ẹran aṣẹ́ńwo) #InYoruba | 0 |
Ọmọ t'ó ní t'óun bá dàgbà, orí ẹyẹlé l'òun ó máa fi mu ẹ̀kọ; orí ẹyẹlé ò ní í jẹ́ k'ó d'àgbà. #EsinOro #Yoruba | 0 |
Wọ́n níkú akọni ní í pa akọni; ikú omi ní í pa ọ̀mọ̀wẹ̀; òwò t'ẹ́dàá bá mọ̀ ní ṣẹ́ ẹ̀dá lẹ́yìn. #AdebayoFaletiODigba #Yoruba #OmoYoobaAtata | 0 |
A ò rí ọyẹ́ o! Pẹ̀lú òjò ànàá t'ó yẹ k'ọ́yẹ́ bolẹ̀ bíi ìrì lónìí. A kò ri o :( | 0 |
@user @user @user @user Aríjẹ nídìí ìbàjẹ́ @user, kí la gbé kí lo jù! Ọ̀rọ̀ rẹ yé mi, ta ni eṣinṣin ò bá gbé bí kò ṣe elégbò, ìjọba ló ń pata sí ọ lẹ́nu, ó ní láti gbè lẹ́yìn wọn. Kú ìgbèléyìn-in o. Àmọ́ òtítọ́ ò ní kí a má sọ òun, ìbéèrè kò fàjà | 0 |
RT @user: @user ...bowo ba tan lowo alakowe... | 0 |
Osan t'ori gbajumo ti ko bo, eranko buburu ni fi iru won je.... #yoruba. | 0 |
Eni nduro wo iseju akan,a pe leti omi...Arindin Olofo #TweetInYoruba https://t.co/xdE6wv87re | 0 |
RT @user: Wòlíì tí yóò gbàdúrà fún wèrè, kò gbọdọ̀ dijú. #EsinOro #OweIgbalode #Yoruba | 0 |
RT @user: Ẹni tó gbé ìlù ẹ̀ kọ́ apá ayé ńbáa lùú, ánbọ̀tórí ẹni gbé tirẹ̀ kọ́ igi tó ṣeré lọ. / Translation >> | 0 |
@user @user Olójú-kòkòrò oníjẹkújẹ ni. Wọ́n máa nfi wé òṣèlú oníwà ìbàjẹ́ tí nkówó jẹ. | 0 |
#LetsPauseAndReflect #Yoruba Ronu! Igbeyin lo ma n ye oloku ada | 0 |
Mo ò rántí enìkan t'ó l'óhun yóò ṣe ọkọ̀ fún ológun Nigeria bí ìjọba bá kówó lé e, wọ́n kọtí ikún, títí tí òyìnbó fi rà á. #IjobaWaKala | 0 |
Child Abusers have done it again. What a disheartening situation. 👉 Yorùbátv ẸGBẸ ỌMỌ OLÚWA BÍ GBOGBO ÀGBÁYÉ Ojú òpó ìkànsíraẹni 🇳🇬🇹🇬🇧🇯🇧🇷🇨🇴🇨🇺🇬🇭🇨🇮 Yoruba TV 🥰😘🔥 #yoruba #yorubatv #yorubaweddings #ebi #asoebi… https://t.co/3fK7s5Yhcb | 0 |
Ojoojúmọ́ ni ọkọ̀ òfuurufú ńjá ní #Nigeria. Kí ló ńṣẹlẹ̀ gan an? #Agagu #Akure #PlaneCrash #Plane #AssociatedAirlineCrash | 0 |