diacritcs
stringlengths 1
36.7k
| no_diacritcs
stringlengths 1
35.5k
|
---|---|
Ìgbésí ayé Sólómọ́nì ọmọ Dáfídì náà jẹ́ àpẹẹrẹ bí ìgbésí ayé Jésù ṣe máa rí . | Igbesi aye Solomoni omo Dafidi naa je apeere bi igbesi aye Jesu se maa ri . |
Tom jẹ́wọ́ pé : “ Ńṣe ni oorun gbé mi lọ . ” | Tom jewo pe : “ Nse ni oorun gbe mi lo . ” |
Ṣé wàá lè gba àwọn nǹkan míì tẹ́ni náà bá sọ fún ẹ gbọ́ nípa àwọn ohun tó túbọ̀ ṣe pàtàkì bí ohun tó o fẹ́ fi ìgbésí ayé rẹ̀ ṣe ? | Se waa le gba awon nnkan mii teni naa ba so fun e gbo nipa awon ohun to tubo se pataki bi ohun to o fe fi igbesi aye re se ? |
Ayọ̀ àti inúdídùn ni a ó rí nínú rẹ̀, ọpẹ́ àti ariwo orín kíkọ | Ayo ati inudidun ni a o ri ninu re, ope ati ariwo orin kiko |
Síbẹ̀ , ṣó burú tí ẹni náà bá sọ pé láti ìbẹ̀rẹ̀ lóun tí máa wo eré náà ? | Sibe , so buru ti eni naa ba so pe lati ibere loun ti maa wo ere naa ? |
Lẹ́yìn ìrìn àjò míṣọ́nnárì ẹlẹ́ẹ̀kẹta tí Pọ́ọ̀lù rìn , ó jábọ̀ fún ẹgbẹ́ olùṣàkóso nípa bí àwọn èèyàn ṣe yí padà . | Leyin irin ajo misonnari eleeketa ti Poolu rin , o jabo fun egbe olusakoso nipa bi awon eeyan se yi pada . |
Mèsáyà máa wọ Jerúsálẹ́mù tiyì - tẹ̀yẹ . | Mesaya maa wo Jerusalemu tiyi - teye . |
Ọ̀pọ̀ yóò wẹ ara wọn mọ́ , wọn yóò sì sọ ara wọn di funfun , a ó sì yọ́ wọn mọ́ . | Opo yoo we ara won mo , won yoo si so ara won di funfun , a o si yo won mo . |
“ Àṣàrò inú ọkàn - àyà mi yóò sì jẹ́ ti àwọn ohun òye . ” — Sáàmù 49 : 3 . | “ Asaro inu okan - aya mi yoo si je ti awon ohun oye . ” — Saamu 49 : 3 . |
Láti ọdún 2001 ni orílẹ̀ - èdè Àméníà ti di ara Ìgbìmọ̀ Ilẹ̀ Yúróòpù . | Lati odun 2001 ni orile - ede Amenia ti di ara Igbimo Ile Yuroopu . |
Kí la lè sọ nípa òfin irú Ẹlẹ́dàá bẹ́ẹ̀ tàbí nípa Ọ̀rọ̀ rẹ̀ tó wà lákọsílẹ̀ ? | Ki la le so nipa ofin iru Eledaa bee tabi nipa Oro re to wa lakosile ? |
Ìgbéraga wọ̀ mí lẹ́wù débi pé mo kọ ìmọ̀ràn táwọn alàgbà fún mi , mo sì fi ìjọ Ọlọ́run sílẹ̀ . ” | Igberaga wo mi lewu debi pe mo ko imoran tawon alagba fun mi , mo si fi ijo Olorun sile . " |
Nígbà tí Jésù kú tó sì gbé ìtóye ẹ̀jẹ̀ rẹ̀ lọ fún Bàbá rẹ̀ lọ́dún 33 Sànmánì Kristẹni la fi ìpìlẹ̀ májẹ̀mú tuntun yìí lélẹ̀ . | Nigba ti Jesu ku to si gbe itoye eje re lo fun Baba re lodun 33 Sanmani Kristeni la fi ipile majemu tuntun yii lele . |
Ìyá rẹ jẹ́ ọmọ ilẹ̀ Nàìjíríà nígbà tí bàbá rẹ jẹ́ ọmọ ilẹ̀ gẹ̀ẹ́sì. | Iya re je omo ile Naijiria nigba ti baba re je omo ile geesi. |
Nígbà tí Jésù wà lórí ilẹ̀ ayé , báwo ló ṣe tẹ̀ lé àpẹẹrẹ Baba rẹ̀ ? | Nigba ti Jesu wa lori ile aye , bawo lo se te le apeere Baba re ? |
Ọmọbìnrin rẹ ni ìwọ kò gbọ́dọ̀ fi fún ọmọkùnrin rẹ̀ , ọmọbìnrin rẹ̀ sì ni ìwọ kò gbọ́dọ̀ mú fún ọmọkùnrin rẹ . ” | Omobinrin re ni iwo ko gbodo fi fun omokunrin re , omobinrin re si ni iwo ko gbodo mu fun omokunrin re . " |
gbọn-ọ́n | gbon-on |
Jèhófà fẹ́ kó o di ọ̀rẹ́ òun . | Jehofa fe ko o di ore oun . |
Àwòrán oníhòòhò máa ń ba gbogbo àwọn tó bá kó sínú páńpẹ́ ẹ̀ láyé jẹ́ ni . | Aworan onihooho maa n ba gbogbo awon to ba ko sinu panpe e laye je ni . |
A lọ síbẹ̀ , wọ́n sì pín fọ́ọ̀mù Ilé Ẹ̀kọ́ Gílíádì lé wa lọ́wọ́ lẹ́yìn ìpàdé náà . | A lo sibe , won si pin foomu Ile Eko Giliadi le wa lowo leyin ipade naa . |
Ní October 1949 — ọdún mẹ́ta lẹ́yìn tí Bill gbé Rose níyàwó àti oṣù mẹ́ta lẹ́yìn tí wọ́n bí Vicki , ọmọbìnrin wọn — wọ́n sọ fún Bill pé kókó ọlọ́yún kan ń dàgbà nínú ọ̀kan lára àwọn tán - án - ná rẹ̀ , wọ́n sì mú kókó náà kúrò . | Ni October 1949 — odun meta leyin ti Bill gbe Rose niyawo ati osu meta leyin ti won bi Vicki , omobinrin won — won so fun Bill pe koko oloyun kan n dagba ninu okan lara awon tan - an - na re , won si mu koko naa kuro . |
Báwo la ṣe lè dáàbò bo ara wa tá ò fi ní ní ẹ̀mí tí kò dára táwọn tí kì í jọ́sìn Jèhófà ní ? | Bawo la se le daabo bo ara wa ta o fi ni ni emi ti ko dara tawon ti ki i josin Jehofa ni ? |
A sáà mọ̀ pé “ ayé ń kọjá lọ , bẹ́ẹ̀ sì ni ìfẹ́kúfẹ̀ẹ́ rẹ̀ , ṣùgbọ́n ẹni tí ó bá ń ṣe ìfẹ́ Ọlọ́run ni yóò dúró títí láé . ” | A saa mo pe “ aye n koja lo , bee si ni ifekufee re , sugbon eni ti o ba n se ife Olorun ni yoo duro titi lae . ” |
Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí | Awon Ohun To Wa Ninu Iwe Yii |
Àwọn tó ń gbé orí àwọn òkè wọ̀nyẹn ní ẹ̀mí aájò àlejò gan - an ni . | Awon to n gbe ori awon oke wonyen ni emi aajo alejo gan - an ni . |
yòò sì wí pé, 'Kì í ṣe àwa ni ẹ̀yin n | yoo si wi pe, 'Ki i se awa ni eyin n |
Nínú ìwádìí kan tí Claude Steiner tó jẹ́ afìṣemọ̀rònú ṣe , ó parí èrò sí pé fífún ẹnì kan ní ìṣírí lọ́rọ̀ àti níṣe ṣe pàtàkì fún un láti ní ìbàlẹ̀ ọkàn láìka ọjọ́ orí rẹ̀ sí . | Ninu iwadii kan ti Claude Steiner to je afisemoronu se , o pari ero si pe fifun eni kan ni isiri loro ati nise se pataki fun un lati ni ibale okan laika ojo ori re si . |
Àwa ńkọ́ ? | Awa nko ? |
Láàárín ọjọ́ díẹ̀ péré , ó lé ní ọ̀kẹ́ mẹ́rin ààbọ̀ [ 90,000 ] èèyàn , ìyẹn ìpín méjì nínú ìpín ọgọ́rùn - ún àwọn àgbàlagbà tí wọ́n kó lọ sáwọn ẹ̀wọ̀n àtàwọn àgọ́ ìṣẹ́níṣẹ̀ẹ́ tí wọ́n sì fẹ̀sùn kàn wọ́n pé wọ́n ń ta ko ìjọba Násì . | Laaarin ojo die pere , o le ni oke merin aabo [ 90,000 ] eeyan , iyen ipin meji ninu ipin ogorun - un awon agbalagba ti won ko lo sawon ewon atawon ago isenisee ti won si fesun kan won pe won n ta ko ijoba Nasi . |
Tó o bá fẹ́ fi ọrẹ ṣètìlẹyìn , jọ̀wọ́ lọ sórí www.jw.org / yo . | To o ba fe fi ore setileyin , jowo lo sori www.jw.org / yo . |
Bákan náà, Bísí Ògúnṣínà (1981:4) ki defined sociology Soṣíọ́lọ́jì báyìí pé: | Bakan naa, Bisi Ogunsina (1981:4) ki defined sociology Sosioloji bayii pe: |
Jèhófà máa ń fi inú rere onífẹ̀ẹ́ tó ní , tàbí ìfẹ́ dídúróṣinṣin rẹ̀ hàn ní onírúurú ọ̀nà . | Jehofa maa n fi inu rere onifee to ni , tabi ife didurosinsin re han ni oniruuru ona . |
dàmáskù | damasku |
Nígbà tí Juan Arias ń sọ̀rọ̀ nípa ipa tí wọ́n ní Màríà Magidalénì kó , ó sọ nínú ìwé ìròyìn Brazil náà , O Estado de S . | Nigba ti Juan Arias n soro nipa ipa ti won ni Maria Magidaleni ko , o so ninu iwe iroyin Brazil naa , O Estado de S . |
Ìwé Sekaráyà 13 : 4 - 6 sọ pé kódà àwọn kan lára àwọn àlùfáà á jáwọ́ nínú ìsìn èké tí wọ́n ń ṣe , wọ́n á sì sẹ́ pé àwọn ò ṣe ìsìn èké rí . — 7 / 15 , ojú ìwé 15 sí 16 . | Iwe Sekaraya 13 : 4 - 6 so pe koda awon kan lara awon alufaa a jawo ninu isin eke ti won n se , won a si se pe awon o se isin eke ri . -- 7 / 15 , oju iwe 15 si 16 . |
( Wo Sáàmù 32 , 23 , 145 , 8 , 30 , 38 , 72 , 51 , 86 àtàwọn àkọlé wọn . ) | ( Wo Saamu 32 , 23 , 145 , 8 , 30 , 38 , 72 , 51 , 86 atawon akole won . ) |
Èyí jẹ́ ká rí i pé Awímáyẹhùn ni Jèhófà . | Eyi je ka ri i pe Awimayehun ni Jehofa . |
Ọlọ́run sọ ọ́ nínú Òfin tí ó fún orílẹ̀ - èdè Ísírẹ́lì pé : “ Ìwọ kò gbọ́dọ̀ ṣe panṣágà . ” | Olorun so o ninu Ofin ti o fun orile - ede Isireli pe : " Iwo ko gbodo se pansaga . " |
Ṣùgbọ́n , ibi tí ìpínlẹ̀ Florida ní orílẹ̀ - èdè Amẹ́ríkà wà lóde òní ló ti bá ara rẹ̀ . | Sugbon , ibi ti ipinle Florida ni orile - ede Amerika wa lode oni lo ti ba ara re . |
( a ) Ìgbà wo ni àsọtẹ́lẹ̀ tí Aísáyà sọ nípa Jerúsálẹ́mù ṣẹ ? | ( a ) Igba wo ni asotele ti Aisaya so nipa Jerusalemu se ? |
Nígbà àtijọ́ , àwọn èèyàn máa ń sin òrìṣà mẹ́ta pa pọ̀ . | Nigba atijo , awon eeyan maa n sin orisa meta pa po . |
Ìbẹ̀rù àìfẹ́ ṣe àṣìṣe lè máà jẹ́ kó o ṣe àwọn nǹkan láṣeyọrí | Iberu aife se asise le maa je ko o se awon nnkan laseyori |
Ẹ máa fi wọ́n kọ́ àwọn ọmọ yín, ẹ máa sọ̀rọ̀ nípa wọn bí ẹ bá jókòó nínú ilé, àti ní ojú ọ̀nà bí ẹ bá ń rìn lọ, bí ẹ bá sùn àti bí ẹ bá jí. | E maa fi won ko awon omo yin, e maa soro nipa won bi e ba jokoo ninu ile, ati ni oju ona bi e ba n rin lo, bi e ba sun ati bi e ba ji. |
Bí èmi kò sì tí mọ̀ bí a tí ń se ìwàdìí nǹkan wọ̀nyí, mo bí i lere pé ṣe ó ń fẹ́ lọ sì Jerúsálémù, kí a sì ṣe ẹjọ́ nǹkan wọ̀nyí níbẹ̀ | Bi emi ko si ti mo bi a ti n se iwadii nnkan wonyi, mo bi i lere pe se o n fe lo si Jerusalemu, ki a si se ejo nnkan wonyi nibe |
Tó o bá gbàdúrà sí Jèhófà , Ẹlẹ́dàá tó jẹ́ Bàbá gbogbo ẹ̀dá lò ń gbàdúrà sí yẹn . | To o ba gbadura si Jehofa , Eledaa to je Baba gbogbo eda lo n gbadura si yen . |
Gan - an gẹ́gẹ́ bí Jèhófà ti ń “ ṣe ọ̀nà àbájáde ” fún wa kí a lè fara da ìdẹwò , bẹ́ẹ̀ náà ni yóò ṣe ọ̀nà àbájáde fún wa nígbà tá a bá dojú kọ àwọn wàhálà tó dà bí ẹ̀gún nínú ẹran ara wa . — 1 Kọ́ríńtì 10 : 13 . | Gan - an gege bi Jehofa ti n " se ona abajade " fun wa ki a le fara da idewo , bee naa ni yoo se ona abajade fun wa nigba ta a ba doju ko awon wahala to da bi egun ninu eran ara wa . -- 1 Korinti 10 : 13 . |
Ojúlówó àǹfààní ló máa ń wá látinú mímọ̀ àti gbígbàgbọ́ pé Jèhófà yóò tipasẹ̀ Jésù ràn wá lọ́wọ́ . | Ojulowo anfaani lo maa n wa latinu mimo ati gbigbagbo pe Jehofa yoo tipase Jesu ran wa lowo . |
[1] Ní ọdún 2018, ó ṣe àkọ́kọ́ eré Nollywood pẹ̀lú eré "Family" tí Lancelot Imasuen kọ́kọ́ ṣe adarí rẹ̀. | [1] Ni odun 2018, o se akoko ere Nollywood pelu ere "Family" ti Lancelot Imasuen koko se adari re. |
Òun ni àkọ́bí mi , a sì mọwọ́ ara wa gan - an ni ; ọ̀pọ̀ nǹkan la máa ń ṣe pa pọ̀ . | Oun ni akobi mi , a si mowo ara wa gan - an ni ; opo nnkan la maa n se pa po . |
“ ‘Àwọn wọ̀nyí ni ìlànà fún ẹranko, ẹyẹ, gbogbo ẹ̀dá alààyè tí ń gbé inú omi àti àwọn ẹ̀dá tí ó ń rìn lórí ilẹ̀. | “ ‘Awon wonyi ni ilana fun eranko, eye, gbogbo eda alaaye ti n gbe inu omi ati awon eda ti o n rin lori ile. |
Ula bí: Ara, Hanieli ati Risia. | Ula bi: Ara, Hanieli ati Risia. |
Àpẹẹrẹ pàtàkì kan tí Pọ́ọ̀lù jíròrò nínú lẹ́tà rẹ̀ ni ti Ábúráhámù , ọkùnrin tó ní ìgbàgbọ́ , tó gbé ayé kí Jèhófà tó fún àwọn ọmọ Ísírẹ́lì ní àkójọ òfin àti ní ọ̀pọ̀ ọdún ṣáájú kí Kristi tó ṣí àǹfààní láti jogún ìyè ti ọ̀run sílẹ̀ . | Apeere pataki kan ti Poolu jiroro ninu leta re ni ti Aburahamu , okunrin to ni igbagbo , to gbe aye ki Jehofa to fun awon omo Isireli ni akojo ofin ati ni opo odun saaju ki Kristi to si anfaani lati jogun iye ti orun sile . |
Lọ sókè àti sódò àwọn òpó Jérúsálẹ́mù Wò yíká, kí o sì mọ̀, kí o sì wá kiri Bí o bá le è rí ẹnìkan, tí ó jẹ́ olóòótọ́ àti olódodo, N ó dárí jìn ìlú yìí | Lo soke ati sodo awon opo Jerusalemu Wo yika, ki o si mo, ki o si wa kiri Bi o ba le e ri enikan, ti o je oloooto ati olododo, N o dari jin ilu yii |
Kí làwọn nǹkan tá a lè ṣe láti fi hàn pé à ń wádìí ohun tí àwa fúnra wa jẹ́ ? | Ki lawon nnkan ta a le se lati fi han pe a n wadii ohun ti awa funra wa je ? |
Alàgbà kan tó ń gbé ní ìlú tí wàhálà náà ti bẹ̀rẹ̀ gan - an ṣàlàyé pé : “ Nǹkan bí ọjọ́ márùn - ún lẹ́yìn tí ìjà náà bẹ̀rẹ̀ ni a ti ṣètò fún iṣẹ́ ìwàásù , ní àárín ìlú àti lágbègbè rẹ̀ . | Alagba kan to n gbe ni ilu ti wahala naa ti bere gan - an salaye pe : “ Nnkan bi ojo marun - un leyin ti ija naa bere ni a ti seto fun ise iwaasu , ni aarin ilu ati lagbegbe re . |
Ó dájú pé ojúṣe tó ń buyì kúnni , tó sì ṣe pàtàkì lèyí jẹ́ pẹ̀lú . | O daju pe ojuse to n buyi kunni , to si se pataki leyi je pelu . |
samosi | samosi |
Gbogbo àwọn tá a dárúkọ yìí ló mọ̀ dájú pé ẹ̀bùn àbínibí tàbí ohun ìní yòówù káwọn ní , tàbí ipò pàtàkì tó wù káwọn wà , iṣẹ́ ìsìn àwọn sí Ọlọ́run ló gbọ́dọ̀ ṣe pàtàkì sáwọn ju iṣẹ́ oúnjẹ òòjọ́ àwọn lọ . | Gbogbo awon ta a daruko yii lo mo daju pe ebun abinibi tabi ohun ini yoowu kawon ni , tabi ipo pataki to wu kawon wa , ise isin awon si Olorun lo gbodo se pataki sawon ju ise ounje oojo awon lo . |
Ẹlẹ́rìí náà sọ pé : “ Mi ò fi bẹ́ẹ̀ rí i kó sunkún rí , àmọ́ ó sunkún lọ́jọ́ tá a jọ sọ̀rọ̀ yìí . ” | Elerii naa so pe : " Mi o fi bee ri i ko sunkun ri , amo o sunkun lojo ta a jo soro yii . " |
Báwo la ṣe lè fàánú hàn bíi ti Jèhófà táwọn èèyàn bá ṣẹ̀ wá ? | Bawo la se le faanu han bii ti Jehofa tawon eeyan ba se wa ? |
Bàbá mi ní tirẹ̀ , Frank How , jẹ́ ọkùnrin jẹ́ẹ́jẹ́ẹ́ , òun ló sì kọ́kọ́ gbógun ti Màmá nítorí ẹ̀sìn tó ń ṣe . | Baba mi ni tire , Frank How , je okunrin jeejee , oun lo si koko gbogun ti Mama nitori esin to n se . |
Ẹ wọ ẹnubodè rẹ̀ tẹ̀yin tọpẹ́,kí ẹ sì wọ inú àgbàlá rẹ̀ tẹ̀yin tìyìn.Ẹ dúpẹ́ lọ́wọ́ rẹ̀,kí ẹ sì máa yin orúkọ rẹ̀. | E wo enubode re teyin tope,ki e si wo inu agbala re teyin tiyin.E dupe lowo re,ki e si maa yin oruko re. |
Màá máa wá àwọn èèyàn lọ ní ìrọ̀lẹ́ o , àmọ́ mo gbọ́dọ̀ máa lọ sí àwọn ìpàdé pàtàkì kan ní ìrọ̀lẹ́ Tuesday àti ìrọ̀lẹ́ Thursday . ” | Maa maa wa awon eeyan lo ni irole o , amo mo gbodo maa lo si awon ipade pataki kan ni irole Tuesday ati irole Thursday . ” |
Ìbéèrè Láti Ọwọ́ Àwọn Òǹkàwé | Ibeere Lati Owo Awon Onkawe |
Kò ju oṣù mẹ́jọ lọ tó bẹ̀rẹ̀ ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì tó fi di akéde aláìṣèrìbọmi , kò sì pẹ́ sí àkókò yẹn tó fi ṣèrìbọmi . | Ko ju osu mejo lo to bere ikekoo Bibeli to fi di akede alaiseribomi , ko si pe si akoko yen to fi seribomi . |
Àmọ́ àjọ yìí kógbá sílé nígbà tí Ogun Àgbáyé Kejì bẹ̀rẹ̀ . | Amo ajo yii kogba sile nigba ti Ogun Agbaye Keji bere . |
Ó sì sun ara ẹran àti awọ rẹ̀ ní ẹ̀yìn ibùdó. | O si sun ara eran ati awo re ni eyin ibudo. |
Ó sì sọ ọ̀wọ̀n náà ní Misipa, nítorí ó wí pé, “Kí OLUWA ṣọ́ wa nígbà tí a bá pínyà lọ́dọ̀ ara wa. | O si so owon naa ni Misipa, nitori o wi pe, "Ki OLUWA so wa nigba ti a ba pinya lodo ara wa. |
dúpẹ́ púpọ̀ lọ́wọ́ kábíyèsí aláṣẹ | dupe pupo lowo kabiyesi alase |
ilẹ̀ ìlérí, nínú àwọn ohun èyí tí mo n yọ̀; bẹ̃ni, èmi sì mọ̀ wí pé Olúwa yíò gba àwọn ọmọkùnrin mi kúrò ní ọwọ́ Lábánì, yíò sì tún mú wọn sọ̀kalẹ̀ sí ọ̀dọ̀ wa nínú ijù. | ile ileri, ninu awon ohun eyi ti mo n yo; beni, emi si mo wi pe Oluwa yio gba awon omokunrin mi kuro ni owo Labani, yio si tun mu won sokale si odo wa ninu iju. |
Ọjà tí a fowó rà, owó la fi ńpa. | Oja ti a fowo ra, owo la fi npa. |
Bí Caroline ṣe rí i pé ó dá òun lóhùn tẹ̀rín - tẹ̀yẹ , ló yáa sọ pé : “ Tóò , jẹ́ kí n ṣàlàyé ohun tí mo fẹ́ bá Ìyáàfin B — sọ . ” | Bi Caroline se ri i pe o da oun lohun terin - teye , lo yaa so pe : " Too , je ki n salaye ohun ti mo fe ba Iyaafin B -- so . " |
Àwọn Olùṣọ́ Àgùntàn Tí Wọ́n Jẹ́ “ Àpẹẹrẹ Fún Agbo ” | Awon Oluso Aguntan Ti Won Je “ Apeere Fun Agbo ” |
Bíbélì rọ̀ ọ́ pé : “ Tọ́ ọ wò , kí [ o ] sì rí i pé Jèhófà jẹ́ ẹni rere ; aláyọ̀ ni abarapá ọkùnrin tí ó sá di í . ” — Sáàmù 34 : 8 . | Bibeli ro o pe : " To o wo , ki [ o ] si ri i pe Jehofa je eni rere ; alayo ni abarapa okunrin ti o sa di i . " -- Saamu 34 : 8 . |
Nǹkan bí ọgọ́rùn - ún kìlómítà lápá gúúsù Sáréfátì ni tọkọtaya kan tí wọ́n jẹ́ ọ̀làwọ́ ń gbé . | Nnkan bi ogorun - un kilomita lapa guusu Sarefati ni tokotaya kan ti won je olawo n gbe . |
Bí ó ti jé̩ pé àfi tí àwo̩n è̩tó̩ àti òmìnira wò̩nyí bá yé ènìyàn nìkan ni a fi lè ní àmús̩e̩ è̩jé̩ yìí ní kíkún, | Bi o ti je pe afi ti awon eto ati ominira wonyi ba ye eniyan nikan ni a fi le ni amuse eje yii ni kikun, |
Gbogbo wa pátá ló yẹ ká máa fìtara kọrin sókè sí Jèhófà , yálà a jẹ́ ọmọdé , àgbàlagbà tàbí ẹni tuntun . | Gbogbo wa pata lo ye ka maa fitara korin soke si Jehofa , yala a je omode , agbalagba tabi eni tuntun . |
Síbẹ̀ , Jèhófà mọrírì ẹ̀mí ìfara - ẹni - jìn tí wọ́n ní bí wọ́n ṣe ń sìn níbikíbi tí àìní bá wà . — Sm . | Sibe , Jehofa moriri emi ifara - eni - jin ti won ni bi won se n sin nibikibi ti aini ba wa . -- Sm . |
Lọ́nà wo ? | Lona wo ? |
ṣólómónì | solomoni |
àdùlámù | adulamu |
Dájúdájú Olúwa ni Olùṣọ lorí | Dajudaju Oluwa ni Oluso lori |
Ẹni tí kò rí ayé rí ní ńsọ pé kò sẹ́ni tó gbọ́n bí òun. | Eni ti ko ri aye ri ni nso pe ko seni to gbon bi oun. |
“ Sísọ̀rọ̀ ní àkókò tí kò tọ́ dà bí ìgbà téèyàn sọ ọ̀rọ̀ burúkú sí ẹlòmíì . ” — Sirppa . | " Sisoro ni akoko ti ko to da bi igba teeyan so oro buruku si elomii . " -- Sirppa . |
Ni màmá mi bá ra ohun ìṣeré kan fún mi tó ṣe é tò pọ̀ , tó sì ṣe é tú palẹ̀ . | Ni mama mi ba ra ohun isere kan fun mi to se e to po , to si se e tu pale . |
Àmọ́ , tí inú wa bá ń dùn sí Ọ̀rọ̀ Jèhófà , a ó kórìíra “ ìfẹ́kúfẹ̀ẹ́ ara àti ìfẹ́kúfẹ̀ẹ́ ojú àti fífi àlùmọ́ọ́nì ìgbésí ayé ẹni hàn sóde lọ́nà ṣekárími . ” | Amo , ti inu wa ba n dun si Oro Jehofa , a o koriira " ifekufee ara ati ifekufee oju ati fifi alumooni igbesi aye eni han sode lona sekarimi . " |
Judith , àbúrò mi obìnrin sì jẹ́ ọmọ ọdún méjì ààbọ̀ . | Judith , aburo mi obinrin si je omo odun meji aabo . |
“ Àwọn àpọ́sítélì adárarégèé ” nínú ìjọ Kọ́ríńtì hu ìwà àìlọ́wọ̀ sí Pọ́ọ̀lù . | “ Awon apositeli adararegee ” ninu ijo Korinti hu iwa ailowo si Poolu . |
Nítorí náà, nítorí yín, a óo ro Sioni bí oko, Jerusalẹmu yóo di àlàpà, ahoro tẹmpili yóo sì di igbó kìjikìji.Dafidi bá pàṣẹ fún Joabu, ati àwọn ọ̀gágun rẹ̀, tí wọ́n wà pẹlu rẹ̀, ó ní, “Ẹ lọ sí gbogbo ẹ̀yà Israẹli, láti Dani títí dé Beeriṣeba, kí ẹ sì ka gbogbo àwọn eniyan tí wọ́n wà níbẹ̀, kí n lè mọ iye wọn.”Àbọ̀ ejò kì í gbé isà. | Nitori naa, nitori yin, a oo ro Sioni bi oko, Jerusalemu yoo di alapa, ahoro tempili yoo si di igbo kijikiji.Dafidi ba pase fun Joabu, ati awon ogagun re, ti won wa pelu re, o ni, “E lo si gbogbo eya Israeli, lati Dani titi de Beeriseba, ki e si ka gbogbo awon eniyan ti won wa nibe, ki n le mo iye won.”Abo ejo ki i gbe isa. |
Sún kẹẹrẹ fa kẹẹrẹ ọkọ | Sun keere fa keere oko |
Ṣe ìtọ́jú wọn títí di ọjọ́ kẹrìnlá oṣù yìí nígbà tí gbogbo ìjọ ènìyàn Israẹli yóò pa ẹran náà ní àfẹ̀mọ́júmọ́. | Se itoju won titi di ojo kerinla osu yii nigba ti gbogbo ijo eniyan Israeli yoo pa eran naa ni afemojumo. |
Lọ́nà wo ? | Lona wo ? |
Jésù sọ fún Màtá pé : “ Ẹni tí ó bá ń lo ìgbàgbọ́ nínú mi , bí ó tilẹ̀ kú , yóò yè , àti olúkúlùkù ẹni tí ó wà láàyè , tí ó sì ń lo ìgbàgbọ́ nínú mi , kì yóò kú láé . ” | Jesu so fun Mata pe : " Eni ti o ba n lo igbagbo ninu mi , bi o tile ku , yoo ye , ati olukuluku eni ti o wa laaye , ti o si n lo igbagbo ninu mi , ki yoo ku lae . " |
Àmọ́ o , ọ̀pọ̀ rẹpẹtẹ nǹkan ló jẹ́ pé kò sí ìtọ́ni kan pàtó nípa wọn nínú Bíbélì . | Amo o , opo repete nnkan lo je pe ko si itoni kan pato nipa won ninu Bibeli . |
․ ․ ․ ․ ․ | . . . . . |
Ìyókù àwọn ọmọ Ísírẹ́lì ka èyí sí ìwà àìṣòótọ́ , wọ́n kà á sí ìṣọ̀tẹ̀ sí Jèhófà . | Iyoku awon omo Isireli ka eyi si iwa aisooto , won ka a si isote si Jehofa . |
Ẹlòmíì tó tún jẹ́ ìṣúra iyebíye ni ọkùnrin kan tó ń jẹ́ Martin . | Elomii to tun je isura iyebiye ni okunrin kan to n je Martin . |
“ Lọ́ọ̀tì yan gbogbo Àgbègbè Jọ́dánì fún ara rẹ̀ , Lọ́ọ̀tì sì ṣí ibùdó rẹ̀ lọ sí ìlà - oòrùn . | " Looti yan gbogbo Agbegbe Jodani fun ara re , Looti si si ibudo re lo si ila - oorun . |
Oun náà lo ṣe ọ̀nà tí mo fi yọ lọ́wọ́ Ẹlẹ́gbára, níbi tí a ti ń sọ̀rọ̀, ó bèèrè ohun tí mo rò pé òun lè fi ràn mi lọ́wọ́ mo sì ròyìn ìyọnu tí mo ti bá pàdé fun un. Lẹ́yìn èyí, ó pe àbúrò rẹ ọkùnrin, nígbà tí ó dé, o wí fún un pé kí o lọ gbé ọkọ̀ wá kí ó tù mí kọjá sí apá kejì odo, wéré wọ́n ti mu ọkọ̀ dé, àti èmi àti oun sì rékojá sí òdì kejìo lápá ibi tí mo wà. Kí a tó bọ sí inú ọkọ̀ ó ti béèrè nípa Fìlásayépọ̀ nítorí ó wí pé ẹgbọ́n òun ni, bàbá rẹ̀ jẹ́ àbúrò bàbá òun àwọn méjéèjì wá jẹ́ àbúrò olókun tíí ṣe alákòóso omi. Ó ní bàbá òun tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ Ayédùbúlẹ̀ ni ẹni t;i wọ́n bí bàbá Fìláswayépọ̀ ń gbé kiri. Ó wí fún mi pé ó yẹ kí a wa Filásayépọ̀ rí, nítorí bí a bá le ríi, iwin tíí ṣe alákòóso fìlà rẹ̀ yóò kó wa yọ. Nígbà tí a gúnlẹ̀ sí òdì kejì tán, ó wí pé kí àbúrò òun tó jẹ́ iwin wá Fìlásayépọ̀ wá nní ibikíbi tí ó bá ti lè rii. Wéré tí ó wí báyìí, ṣe ni àbúrò rẹ̀ rá mọ́ wa lójú, nígbà tí o sì fi máa tó ìsẹ́jú mẹ́ta ṣe ni mo rí i tí o ń fò bọ̀ lófurufú tí ó gbé fìlàsayépọ̀ lé èjìká, tí ó gbé e kalẹ̀ lọdọ wa. Ìgbà tí iwin yìí rí fìlásayépọ̀ wọ̀n yọ̀ mọ́ ara wọn, wọ́n sì kí ara wọn dáadáa. Lẹ́yìn náà ó ni ki filásayépọ̀ pe iwin inú fila rẹ̀ fun òun, onítọ̀ún sì ṣe bẹ́ẹ̀. Nígbà tí iwin náà dé, kò ga púpọ̀, o sì sanra o ni iké ńlá kan lẹ́yìn. Òun ati obìnrin yìí sọ̀rọ̀ sí ara wọn ní èdè tì n kò gbọ rí, lẹ́yìn náà ni iwin tii ṣe alákòóso filà yìí bẹ̀rẹ̀, tí o ní ki n jókòó lé òun lẹ́yìn, nígbà tí mo sì ṣe bẹ́ẹ̀, wéré ni mo bá ara mi ni ofuurfú tí o ń fò lọ pẹ̀lú mi. Àyà mi kọ́ já ṣùgbọ́n ó ni ki n dì mọ́ òun lẹ́yìnn dáadáa kì n má ba à já lulẹ̀ mo rọra dọ̀bálẹ̀ lé e lẹ́yìn mo di iké ẹ̀yìn rẹ̀ mú dáadáa. Iwin náà ni irun lára bi ti ẹranko gan-an ni, irun wọ̀nyí ni mo si di mọ́ pẹ̀lú iké ẹ̀yìn rẹ̀ tí kò jẹ́ kí n já ṣubú. Nígbà tí ó pẹ́ díẹ̀ ó gbé mi sọ̀kalẹ̀ sí ojú ọ̀nà Igbó Elégbèje, ó sì wí fún mi pé a ti kúró ní àgbègbè ibi tí Ẹlẹ́gbára máa ń dé, ṣùgbọ́n ó wí fún mi ki n má kúrò nibi tí òun gbé mi s’’i nítorí òun ń lọ máa gbé àwọn yòókù lọ́kọ́ọ̀kan wá. | Oun naa lo se ona ti mo fi yo lowo Elegbara, nibi ti a ti n soro, o beere ohun ti mo ro pe oun le fi ran mi lowo mo si royin iyonu ti mo ti ba pade fun un. Leyin eyi, o pe aburo re okunrin, nigba ti o de, o wi fun un pe ki o lo gbe oko wa ki o tu mi koja si apa keji odo, were won ti mu oko de, ati emi ati oun si rekoja si odi kejio lapa ibi ti mo wa. Ki a to bo si inu oko o ti beere nipa Filasayepo nitori o wi pe egbon oun ni, baba re je aburo baba oun awon mejeeji wa je aburo olokun tii se alakooso omi. O ni baba oun ti oruko re n je Ayedubule ni eni t;i won bi baba Filaswayepo n gbe kiri. O wi fun mi pe o ye ki a wa Filasayepo ri, nitori bi a ba le rii, iwin tii se alakooso fila re yoo ko wa yo. Nigba ti a gunle si odi keji tan, o wi pe ki aburo oun to je iwin wa Filasayepo wa nni ibikibi ti o ba ti le rii. Were ti o wi bayii, se ni aburo re ra mo wa loju, nigba ti o si fi maa to iseju meta se ni mo ri i ti o n fo bo lofurufu ti o gbe filasayepo le ejika, ti o gbe e kale lodo wa. Igba ti iwin yii ri filasayepo won yo mo ara won, won si ki ara won daadaa. Leyin naa o ni ki filasayepo pe iwin inu fila re fun oun, onitoun si se bee. Nigba ti iwin naa de, ko ga pupo, o si sanra o ni ike nla kan leyin. Oun ati obinrin yii soro si ara won ni ede ti n ko gbo ri, leyin naa ni iwin tii se alakooso fila yii bere, ti o ni ki n jokoo le oun leyin, nigba ti mo si se bee, were ni mo ba ara mi ni ofuurfu ti o n fo lo pelu mi. Aya mi ko ja sugbon o ni ki n di mo oun leyinn daadaa ki n ma ba a ja lule mo rora dobale le e leyin mo di ike eyin re mu daadaa. Iwin naa ni irun lara bi ti eranko gan-an ni, irun wonyi ni mo si di mo pelu ike eyin re ti ko je ki n ja subu. Nigba ti o pe die o gbe mi sokale si oju ona Igbo Elegbeje, o si wi fun mi pe a ti kuro ni agbegbe ibi ti Elegbara maa n de, sugbon o wi fun mi ki n ma kuro nibi ti oun gbe mi s''i nitori oun n lo maa gbe awon yooku lokookan wa. |
[ Àwòrán tó wà ní ojú ìwé 15 ] | [ Aworan to wa ni oju iwe 15 ] |