url
stringlengths
37
41
id
stringlengths
1
5
text
stringlengths
2
134k
title
stringlengths
1
120
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=16950
16950
Biyi Bandele Biyi Bandele (Ọjọ́ kẹtàlá Oṣù Ọ̀wàrà Ọdún 1967 ni wọ́n bí i, tí ó sì kú ní ọjọ́ kejè, Oṣù Ògún, Ọdún 2022). Òǹkọ̀wé, àti òṣeré ọmọ Nàìjíríà ni. Ó ti kọ ọ̀pọ̀lọpọ̀ ìwé ìtàn àròsọ , ó bẹ̀rẹ̀ pẹ̀lú  The Man Who Came in From the Back of Beyond ní ọdún 1991, bákan náà ni ó kọ àwọn eré onísẹ́ kí ó tó wá gbájúmọ́ fíìmù ṣíṣe. àkọ́já ewé rẹ̀ gẹ́gẹ́ bíi olùdarí  dárí ni Half of a Yellow Sun ní ọdún 2013, tí ó jẹ́ ìwé ìtàn àròsọ Chimamanda Ngozi Adichie Ìbẹ̀rẹ̀ ayé rẹ̀. Yorùbá ni àwọn òbí Bandele, ìlú Kafancha ní Kaduna ni wọ́n bí i sí ní ọdún 1967. Bàbá rẹ̀ Solomon Bandele-Thomas jẹ́ àgbà-ọ̀jẹ̀ tí ó ṣe ìpolongo Burma ní ogun àgbáyé kejì nígbà tí Naijiria ṣì wà lábẹ́ àkóso àwọn Bìrìtìkó. Ọdún méjìdínlógún àkọ́kọ́ ìgbésí ayé ni Bándélé lò ni àárín-gbùngbùn àríwá Orílẹ̀èdè kí ó tó wá lọ sí ìlú Èkó, ní ọdún 1987, ó kẹ́kọ̀ọ́ nípa eré onísẹ́ ni Yunifásítì Ọbáfẹ́mi Awólọ́wọ̀ Ilé - Ifẹ̀[1],  [4]ó kọ ìwé ìtàn àròsọ rẹ̀ àkọ́kọ́. "[5]Ó gbégbá orókè nínú idije International Student Playscript ní ọdún 1989 pẹ̀lú iṣẹ́ rẹ̀ tí wọ́n kò tẹ̀ jáde Rain[6] kí ó tó gba àmì ẹ̀yẹ British Council Lagos Award ní ọdún 1990 fún àkójọpọ̀ ewì.  Ó lọ sí Ìlú London ní ọdún 1990, ní ọmọ ọdún méjìlélógún pẹ̀lú ìwé iṣẹ́ ìtàn srosoyrẹ̀ méjì. Wọ́n tẹ àwọn ìwé rẹ̀ jáde, Royal Court Theatre sì fún ní...  Ní ọdún 1992, ó gba àmì ẹ̀yẹ Arts Council of Great Britain Writers Bu Bursar ithenáti tẹ̀síwájú nínú ìwé kíkọ rẹ̀ [8]. IṢẸ́. Iṣẹ́ kíkọ Bándélé kó àkóyawọ́ lórí ìtàn àròsọ, tíátà, ìròyìn, tẹlifíṣàn, fíìmù àti rédíò. Ó siṣẹ́ pẹ̀lú Royal Court Theatre àti Iléeṣé Royal Shakespeare, bákan náà ló kọ iṣẹ́ dírámà orí rédíò àti fíìmù fún tẹlifíṣàn. [10]Lára àwọn iṣẹ́ rẹ̀ ni: Rain;[11] Marching for Fausa (1993); Resurrections in the Season of the Longest Drought (1994); Two Horsemen (1994) tí wọ́n yàn gẹ́gẹ́ bí eré tí ó peregedé jùlọ ní London ní ọdún 1994. Death Catches the Hunter àti Me and the Boys (tí wọ́n tẹ̀ jáde nínú fọ́lọ́mù kìn-ín-ní, ọdún 19951995); àti Oroonoko, Aphda Behn èyí jẹ́ ìṣe àtúndá ìwé náà adaptation [12] ní ọdún 1997, ó ṣe àṣeyọrí Ìwé Chinua Achebe "Things fall apart" gẹ́gẹ́ bí dírámà. Àwọn ìtàn Brixton. Bandele ṣe iṣẹ́ àtúndá ìwé ìtàn àròsọ tara rẹ̀ The Street sí eré ìtàgé,  The Street ní ọdún 1999, tí wọ́n fi lọ́lẹ̀ ni ọdún 2001 premiered in 2001, tí ó sì jáde nínú fọ́lọ́mù kìn-ín-ní àti eré onísẹ́ rẹ̀ Happy Birthday Mister Dekaand was published in  tí ó gbé jáde ní 1999. Bákan náà ni ó ṣe iṣẹ́ àtúndá Lorca Yerma ní ọdún volume with 2001. Ó siṣẹ́ Olùkọ́ òǹkọ̀wé pẹ̀lú Iléeṣé Tíátà Talawa ni odun 1994 sí 1995, [14],bákan náà ló ṣisẹ́ gẹ́gẹ́ bíi ọ̀ǹkọ̀tàn eré onísẹ́ pẹ̀lú Royal National Theatre Studio ní ọdún 1996 [15].  Ọmọ ẹgbẹ́ Wilson ni Kọ́lẹ́jì Churchill, Yunifásítì Cambridge  ní 2001."[16]. Bákan náà ló kópa gẹ́gẹ́ bí Royal Literary Fund Resident Playwright ni Tíátà Bush ní ọdún 2002 sí 2003. [1] [17]. Bandele ti kọ lórí ipa tí iṣẹ́ John Osborne - Back in anger lórí rẹ̀, tí ó rà ní san-án díẹ̀ díẹ̀ ní ojú irin ní Apá Àríwá Nàìjíríà. IKÚ. Bandele kú ní ìlú Èkó ní ọjọ́ kejè, Oṣù Ògún, Ọdún 2022 ni ọmọ ọdún mẹ́rinléláàdọ́ta. Okùnfà ikú rẹ̀ kò tíì di mímọ̀. ÀKÓJỌPỌ̀ ÌWÉ. ÀKÓJỌPỌ̀ FÍÌMÙ
Biyi Bandele
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=16951
16951
Charles Bodunde Charles Bodunde je olukowe omo ile Naijiria.
Charles Bodunde
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=16952
16952
John Pepper Clark Nigerian poet and playwright (1935–2020) John Pepper Clark-Bekederemo (ojoibi April 6, 1935 tosi ku ni ọjọ mẹtala óṣu October ọdun 2020) je olukowe omo ile Naijiria. Arakunrin naa ni órukọ rẹ ma njade nigba toba kọ iwè gẹgẹbi J.P. Clark ati John Pepper Clark. Igbesi Ayè Arakunrin naa. John ni a bisi Kiagbodo,ilú naigiria fun Baba rẹ to jẹ ọmọ ilè Ijaw ati Iya rẹ to jẹ ọmọ ilẹ Urhobo. Nigba ti arakunrin naa jade lati ilè iwè giga ti Ibadan ni ó ṣiṣẹ gẹ̀gẹbi Officer ti Information ni ministry ti information ati research fellow ni Institute ti imọ ẹkọ ilẹ Africa ni ilè iwè giga ti Ibadan. Ni ọdun 1982, John ati Iyawó rẹ Ẹbun Odutola (Professor ati óludari tẹlẹ ri) da theatre ti PEC Repertory silẹ ni ilú eko. Clark ku si ilè iwosan to wa ni eko ni ọjọ kẹkatala óṣu October ni ọdun 2020. Ẹkọ. Clark lọsi ilè iwè Native Authority ni Okrika ni ijọba ibilẹ ti Burutu, ilè iwè ti Ijọba ni Ughelli lẹyin ló tẹsiwaju lọsi ilè iwè giga ti Ilú Ibadan lati kẹẹkọ lọri imọ ede gẹẹsi. Arakunrin naa fun aimoyè ọdun lóti jẹ professor ti èèdè gẹẹsi ni ilè iwè giga ti Eko to si fẹyinti ni ọdun 1980. Clark tigba ipó professor ni ilè iwè giga ti Yale ati Wesleyan ni ilú United States. Ami Ẹyẹ ati Idanilọla. Clark gba Ami Ẹyẹ ti National Order of merit ti ilẹ naigiria lati ọdọ ilè iwè giga ti Howard lóri iwè rẹ "The ozidi Saga ati Akójọpọ Ere ati Ewi lati ọdun 1958-1988. Ni ọjọ kẹfa, óṣu December ni ọdun 2011 ni ayẹ Ayè Professor John Pepper Clark pẹlú ayẹyẹ to waye ni Ikoyi. Ni ọdun 2015 ni Awọn ọdọ ólukọwè ti ilẹ naigiria labẹ akoso Wole Adedoyin da ẹgbẹ JP clark ti Literay lati igbè iṣẹ Clark larugẹ.
John Pepper Clark
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=16953
16953
Olumbe Bassir Olumbe Bassir je olukowe omo ile Naijiria.
Olumbe Bassir
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=16954
16954
Folasayo Dele-Ogunrinde Folasayo Dele-Ogunrinde (1968 - 2013) je olùkọ̀wé ati awọn ẹya òṣeré omo ile Naijiria.
Folasayo Dele-Ogunrinde
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=16955
16955
Umaru Dembo Umaru Dembo je olukowe omo ile Naijiria.
Umaru Dembo
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=16956
16956
Philip Effiong Philip Efiong (also spelled Effiong, November 18, 1925 – November 6, 2003) je omo ologun to tifeyinti lati Ile-ise Ajagun Oripapa Naijiria ati ikan ninu awon asagun orile-ede Biafra alaisimo nigba Ogun Abẹ́lé Nàìjíríà nigba to di Igbakeji Aare ile Biafra si Odumegwu Ojukwu ati Aare ile Biafra fun ojo marun leyin ti Ojukwu salo. Efiong ni eni ti o teriba Biafra fun Naijiria.
Philip Effiong
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=16957
16957
Michael Echeruo Michael Joseph Chukwudalu Echeruo tí wọ́n bi ni ọjọ kẹrinla oṣù kẹta ọdún 1937 je olukowe, ọjọgbọn,alariwisi awọn iwe lítíréṣọ̀ ọmọ ìlú Umunumo, ìjọ́bá Ehime-Mbano, Ipínlè Imo ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.
Michael Echeruo
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=16958
16958
Cyprian Ekwensi Cyprian Ekwensi jẹ́ òǹkọ̀wé ọmọ Orílẹ̀èdè Nàìjíríà. ÌBẸ̀RẸ̀PẸ̀PẸ̀ AYÉ ÀTI Ẹ̀KỌ́. Cyprian Odiatu Duaka Ekwensi jẹ́ ọmọ ilẹ̀ Ìgbò tí wọ́n bí sí ìlú Minna, Ìpínlẹ̀ Niger. Ọmọ bíbí ìlú Nkwelle Ezunaka ní Ìjọba ìbílẹ̀ Oyi, Ipinle Anambra, Nàìjíríà. Bàbá rẹ̀ ni David Anadumaka, apàlọ́ àti ọdẹ aperin. Ekwensi lọ sí Government College ní Ìbàdàn, Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́, Achimota College ní Ghana àti Iléẹ̀kọ́ ìmọ̀ ajẹmọ́-igbó Ìbàdàn, leyin náà ló ṣisẹ́ gẹ́gẹ́ bí òṣìṣẹ́ asọ́gbó fún ọdún méjì. Bákan náà ló lọ sí Ilé-ẹ̀kọ́ṣẹ́ Yaba Technical Institute, àti Iléẹ̀kọ́ nípa oògùn ní ìlú Èkó, Lagos School of Pharmacy àti Iléẹ̀kọ́ Chelsea nípa oògùn  ní Yunifásítì ti London.  Ó siṣẹ́ Olùkọ́ ní Kọ́lẹ́jì Igbóbì (Igbóbì College) ẸBÍ. Ekwensi fẹ́ Eunice Anyiwo, wọ́n sì bí ọmọ márùn-ún pẹ̀lú ọ̀pọ̀lọpọ̀ ọmọọmọ, lára wọn ni Cyprian Ikechi Ekwensi tí wọ́n sọ nù orúkọ bàbá bàbá rẹ̀ àti Adrianne tí i ṣe ọmọọmọ tí ó dàgbà jù IṢẸ́. Wọ́n yan Ekwensi ní olórí ajẹmọ́-àwòmọ́ ní Iléeṣé Iroyin Orílẹ̀èdè Nàìjíríà (Nigerian Broadcasting Corporation), bákan náà ni ẹ̀ka ìròyìn yàn án sípò ni àsìkò ìjọba Olómìnira àkọ́kọ́. Ó padà di olùdarí ẹ̀ka náà. Ó fi iṣẹ́ sílẹ̀ ní ọdún 1966 ṣáájú ogun Abẹ́lé. Ó kó àwọn ẹbí rẹ̀ padà sí Enugu. Bákan náà ló jẹ́ alága Àjọ fún ìpolongo ìlú Biafra. Ekwensi tí kọ ogúnlọ́gọ̀ àwọn ìtàn kéékèèké, eré onísẹ́ fún rédíò àti tẹlifíṣàn àti ọ̀pọ̀lọpọ̀ ìwé ìtàn àròsọ pẹ̀lú àwọn ìwé ọmọdé. IKÚ. Ekwensi di olóògbé ni ọjọ́ kẹrìn, Oṣù Ọ̀wàrà  Ọdún 2007 ní Niger Foundation ní ìlú Enugu níbi tí ó ti lọ ṣe iṣẹ́ abẹ fún àìsàn tí wọ́n kó sọ di mímọ̀. Ẹgbẹ́ àwọn Òǹkọ̀wé fẹ́ fún ní àmì ẹ̀yẹ ṣáájú ikú rẹ̀, wọn padà fi ṣe ìyẹ́sí fún un lẹ́yìn ikú rẹ̀ ÌTỌ́KASÍ. "Cyprian Ekwensi dies at 86". Daily Trust online. 6 November 2007. Retrieved 21 November 2007. "Nigeria Today Is Like A Yarn By Cyprian Ekwensi -". The NEWS. 1 December 2021. Retrieved 6 March 2022. Adenekan, Shola (11 November 2007). "Prolific Writer Who Chronicled Modern Life in West Africa". The New Black Magazine online. Retrieved 21 November 2007. Gérard, Albert S. (1986). European-Language Writing in Sub-Saharan Africa. John Benjamins Publishing Company. p. 654. ISBN 963-05-3834-2. "Cyprian Ekwensi". Encyclopedia of World Biography. Thomson Gale. CHUKA NNABUIFE (29 October 2009). "Authors convention begins in Minna". Nigerian Compass. Retrieved 9 November 2009.[permanent dead link] "Ekwensi, Cyprian". Africana: The Encyclopedia of the African and African American Experience. Running Press. 2003. pp. 226–227. ISBN 0-7624-1642-4. Gérard, p. 656. "Jagua Nana's Daughter". Michigan State University Press. Archived from the original on 10 May 2007. Retrieved 21 November 2007. "ANA plans post humous award for Ekwensi". The Tide Online. Rivers State Newspaper Corporation. 11 November 2007. Archived from the original on 17 July 2011. Retrieved 21 November 2007.
Cyprian Ekwensi
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=16959
16959
Buchi Emecheta Nigerian writer Buchi Emecheta je olukowe omo ile Naijiria ta bini óṣu July ọdun 1944 to si ku ni ọjọ kàrunlèèlogun, óṣu January ni ọdun 2017. Aràbinrin naa bẹrẹ si ni gbe ilẹ UK lati ọdun 1962 nibi to tin kọ lóri plays, itan ati nipa awọn ọmọde Ígbèsi Àyè Àràbinrin naa. Buchi Emecheta ni à bini óṣu july, ọdun 1944 si ilú Eko fun Alice Okwuekwuhe Emecheta ati Jeremy Nwabudinke. Awọn óbi arabinrin naa wa lati Umuezeokolo. Ibusa ni Ipinlẹ Delta. Baba olukọwè naa jẹ óṣiṣẹ ti Railway ati Amọ ikan Arabinrin naa wa lara ọmọ ẹgbẹ ti ilè british secretary advisory council race ni ọdun 1979 Ni ọdun 1960, Arabinrin naa fẹ Sylvester Onwordi to si bi ọmọ ọkunrin ati óbinrin. Onwordi lọsi ilè iwè ni ilú london ti Emecheta ati awọn ọmọ rẹ si darapọ mọ ni ọdun 1962. Larin ọdun mẹfa, Emecheta bi ọmọ mààrun; ọmọ óbinrin mẹta ati ọmọ ọkunrin meji. Igbèyawó arabinrin naa koro to si kun fun jagidigan eleyi lo mu kuro lọdọ ọkọ rẹ to si awọn ọmọ rẹ dani. Ẹkọ. Nitóri ipó tiwọn fi awọn óbinrin sini awujọ, aburó Buchi ló kọkọ lọsi ilè iwè ṣugbọn lẹyin arọwa fub awọn óbi buchi ni ó to lọsi ilè iwè missionary ti awọn óbinrin lẹyin ọdun kan ni Emecheta gba ẹkọ ọfẹ lati lọsi ilè iwè methodist ti awọn óbinrin ni Yaba. Buchi gba B.Sc. lori imọ sociology ni ọdun 1972 ni ilè iwè giga ti london lẹyin naa lo gba PhD ni ilè iwè giga naa ni 1991. Ami Ẹyẹ ati Idanilọla. Arabinrin naa gba idanilọla lóri literature rẹ to si gba ẹbun ti Jock Campbell ni ọdun 1978 fun iwè rẹ ti akọlè naa jẹ "Ẹrú Óbinrin". Buchi wa lori magazine ti Granta to da lóri awọn ólukọwè ọdọ to darajulọ ti ọdun 1983. Buchi gba doctorate ta fi da lọla lori literature lati ọdọ ilè iwè giga ti Farleigh Dickinson ni ọdun 1992. Ni óṣu September, ọdun 2004 Buchi wa ninu Awóran ti "A Great Day in London" to da lóri awọn ólúkọwẹ alawọ dudu ati funfun to kopa ninu itẹsiwaju literature ti ilẹ british. Ni ọdun 2005, Buchi ni a da lọlà OBE lóri iṣẹ ribi ribi tó ṣè lori literature.
Buchi Emecheta
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=16960
16960
Olaudah Equiano Olaudah Equiano(c. 1745 – 31 March 1797), jẹ́ ọmọ bíbí Igbo tí wọ́n kó lẹ́rú nígbà okowò ẹrú. Igbèsi Ayè Àràkunrin naa. Equiano ni a bini Essaka, Eboe ni ilẹ Benin ni ọdun 1745 to si kere julọ ninu awọn ọmọ ti baba rẹ bi. Equiano ni awọn ọga rẹ ninu oko ẹru sọ ni lórukọ lèèmeji, oun jẹ Michael nigba to wa ninu ọkọ óju ọmi ti awọn ẹru to gbè lọ si ilẹ́ america atipè ẹni to ra lẹru lakọkọ sọ ni Jacob. Mary Guerin ati aburó rẹ to jẹ mọlẹbi fun ọgà to ra Equiano lẹru kọ ni èdè gẹẹsi. Ni óṣu December ọdun 1762, pascal ta Equiano lẹru fun Captain James Doran ti Charming Sally ni Gravesend nibi to ti lọ si Caribbean lẹyin naa ni Montserrat ni Islands ti Leeward nibi ti wọn ti ta arakunrin naa fun Robert King to jẹ olokowo ni Caribbean ṣugbon to wa lati ilu Philadelphia. Ni ọjọ keje, óṣu April ọdun 1792, Equiano fẹ Sussanah Cullen ni ilè ijọsin ti St Andrew ni Soham, Cambridgeshire ti wọn si bi ọmọ óbinrin meji; Anna Maria (1793-1797) ati Joanna (1795-1857) ti wọn ṣè iribọ ọmi ni church ti Soham. Iyawó Equiano Susannah ku ni óṣu february ọdun 1796 ni ọmọ ọdun mẹrin lèèlọgbọn. Ọmọ óbinrin Equiano agba ku ni ọmọ ọdun mẹrin ni ọdun 1797 ti wọn sin si church ti St Andrew ni Chesterton, Cambridge. Joanna Vassa tọ jẹ ọmọ óbinrin keji ti equiano bi fẹ Henry Bromley ni 1821 ti wọn si awọn mejèèji si itẹ ti Abney Park ni Stoke Newington, London. Equiano ku ni ọjọ kan lèèlọgbọn óṣu march ni ọdun 1797 ti wọn si sọ nipa iku rẹ ninu iwè iroyin ti ilẹ british ati america. Wọn si arakunrin naa si Whitefield Tabernacle ni ọjọ kẹfa óṣu April ọdun 1797. Idanilọla. Óṣèrè lọkunrin ilẹ Gambia Louis Mahoney ṣèrè lóri Equiano ninu television ti BBC lori ijagbara ati ominira tita ati rira ẹru ni ọdun 1975. Crater to wa ni Mercury ni a sọ ni "Equiano" ni ọdun 1976. Ni óṣu November, ọdun 1996 Equiano Society ni wọn da silẹ ni ilú london lati fi yẹ arakuneim naa si. Equiano ni ṣè afihan rẹ ninu ere agbelewó ti Amazing grace lati ọdọ ólórin ilẹ senegal Youssou N'Dour ni ọdun 2006. Ni óṣu july, Equiano ni church ti England yẹ si fun ijagbara ninu óminira tita ati rira ẹru. Ni ọdun 2008, ere equiano ni awọn ọmọ ilè iwè ti Edmund waller mọ si Telegraph Hill, lower park ni New cross ni ilú London. Ni ọdun 2022, cambridge yẹ Equiano si pẹlu sisọ Riverside Bridge si Equiano Bridge. Ni ọdun 2022, ere agbelewó nipa igbesi aye Olaudah Equiano waye lati ọdọ Radio ti BBC.
Olaudah Equiano
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=16963
16963
Rosemary Esehagu Rosemary Esehagu je olukowe omo ile Naijiria.
Rosemary Esehagu
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=16964
16964
Femi Euba Femi Euba je olukowe omo ile Naijiria.
Femi Euba
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=16965
16965
Chielozona Eze Chielozona Eze je olukowe omo ile Naijiria.
Chielozona Eze
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=16966
16966
Vera Ezimora Vera Ezimora je olukowe omo ile Naijiria.
Vera Ezimora
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=16967
16967
MacAulay Oluseyi Akinbami MacAulay Oluseyi Akinbami je olukowe omo ile Naijiria.
MacAulay Oluseyi Akinbami
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=16968
16968
Aderinola Richardson Aderinola Richardson je olukowe omo ile Naijiria.
Aderinola Richardson
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=16969
16969
Daniel Olorunfemi Fagunwa
Daniel Olorunfemi Fagunwa
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=16970
16970
Dan Fulani Dan Fulani je olukowe omo ile Naijiria.
Dan Fulani
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=16971
16971
Helon Habila Helon Habila (ojoibi 1967) je olukowe omo ile Naijiria ti arakunrin naa gba ẹbun ti Caine ni ọdun 2001. Ígbèsi Àyè Àrakunrin naa. Helon Habila ni a bini Kaltungo,ipinlẹ Gombe, ilẹ Naigiria. Ni ọdun 2002, Habila lọsi ilú England ni ọdun 2002 ti arakunrin naa di fellow ti akọwè ilẹ africa ni ilè iwè giga ti East Anglia. Ni ọdun 2005, Chinua Achebe pè Habila lati di fellow rẹ akọkọ ni college ti Bard. Lati óṣu July 2013 di óṣu June 2014 Habila di fellow ti DAAD Fellow ni Berlin, Germany. Arakunrin naa ni wọn fi ṣè adajọ ninu ẹbun ti Etisalat lori literature ni ọdun 2016. Ẹkọ. Helen kẹẹkọ lóri èdè gẹẹsi ati imọ literature ni ilè iwè giga ti jos lẹyin naa lo ṣiṣẹ ólukọ ni ninu Federal polytechnic ti Bauchi. Ami Ẹyẹ ati Idanilọla. Ni ọdun 2000 Ami ẹyẹ ti ẹgbẹ awọn ólórin ti ilẹ Naigiria apapọ ewi. Ni ọdun 2001 Ẹbun ti Caine, "Love Poems". Ni ọdun 2003, Ẹbun ti Commonwealth awọn akọwè ti ilẹ africa, Waiting for an Angel. Ni ọdun 2007 Ẹbun ti Emily Clark Balch, "The Hotel Malogo". Ni ọdun 2008 Ami ẹyẹ ti Library of Virginia Literary fun for Fiction, Measuring Time. Ni ọdun 2011, Ẹbun ti Commonwealth awọn akọwè Oil on Water. Ni ọdun 2012 Ami ẹyẹ ti iwè Orion, Oil on Water. Ni ọdun 2020, Ẹbun ti James Tait Black Memorial, Travelers.
Helon Habila
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=16972
16972
Uzodinma Iweala Uzodinma Iweala (ojoibi November 5, 1982) je olukowe omo ile Naijiria.
Uzodinma Iweala
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=16973
16973
J.P. Clark
J.P. Clark
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=16974
16974
Nkem Nwankwo Nkem Nwankwo je olukowe omo ile Naijiria.
Nkem Nwankwo
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=16975
16975
Flora Nwapa Florence Nwanzuruahu Nkiru Nwapa je olukowe omo ile Naijiria.
Flora Nwapa
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=16976
16976
Olu Obafemi Olu Obafemi je olukowe omo ile Naijiria.
Olu Obafemi
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=16977
16977
Odia Ofeimun Odia Ofeimun je olukowe omo ile Naijiria.
Odia Ofeimun
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=16978
16978
Christopher Okigbo Christopher Ifekandu Okigbo (1930–1967) je olukowe omo ile Naijiria.
Christopher Okigbo
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=16979
16979
Wole Oguntokun Wole Oguntokun jẹ́ Ònkọ̀wé, adarí eré orí-ìtàgé, agbẹjọ́rò àti oníṣẹ́ Ìwé Ìròyìnìwé ìròyìn ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.
Wole Oguntokun
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=16980
16980
Ben Okri Ben Okri OBE FRSL (ojoibi 15 March 1959) je olukowe omo ile Naijiria.
Ben Okri
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=16981
16981
Kole Omotosho Bankole (Kole) Ajibabi Omotoso (1943-2023) je olukowe omo ile Naijiria.
Kole Omotosho
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=16982
16982
Tess Onwueme Tess Onwueme je olukowe omo ile Naijiria.
Tess Onwueme
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=16983
16983
Osonye Tess Onwueme
Osonye Tess Onwueme
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=16984
16984
Dennis Osadebay Dennis Chukude Osadebay (June 29, 1911—December 26, 1994) je Asiwaju tele agbegbe Nigeria tele Arin-Apaiwoorun ati olukowe omo ile Naijiria.
Dennis Osadebay
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=16985
16985
Niyi Osundare Niyi Osundare (bí ni ọjọ́ kejìlá, Oṣù Ẹ̀rẹnà, Ọdún 1947) jẹ́ onímọ̀ èdè, akéwì, onísẹ́ lámèyítọ́ àti eléré onísẹ́ ọmọ Orílẹ̀èdè Nàìjíríà. Ìbẹ̀rẹ̀ Pẹ̀pẹ̀ ayé rẹ̀. Nìyí Ọ̀sundare jẹ́ aṣáájú akéwì nílẹ̀ Adúláwọ̀, eléré-onísẹ́, onímọ̀ èdè àti onísẹ́ lámèyítọ́. Ìlú Ìkẹ́rẹ́ Èkìtì ní apá ìwọ̀ oòrùn Nàìjíríà ni wọ́n ti bí i ni ọjọ́ kejìlá, Oṣù Ẹ̀rẹnà, Ọdún 1947. Òrìṣà tó ò gún ewì rẹ̀ ni ewì alohùn nínú àṣà Yorùbá rẹ̀, èyí ló jẹ́ kí ìwọ̀nùbọ̀nú wà nínú iṣẹ́ rẹ̀ àti àṣà ewì àgbáyé yòókù, lára wọn ni Ilẹ̀ Adúláwọ̀, Amẹ́ríkà, Amẹ́ríkà - Látìnì, Éyísà àti Yúróòpù. Ó táko ìdúnmokò mọ́ ọ̀rọ̀ sísọ bákan náà àwọn iṣẹ́ àtinúdá àti àròjinlẹ̀ ni ìbáṣepọ̀ pẹ̀lú ìjàǹgbara òṣèlú, òmìnira àti ìfọwọ́sowọ́pọ̀ àwọn Adúláwọ̀ àti agbègbè. Ó ti gba ọ́pọ̀lọpọ̀ àmì-ẹ̀yẹ lára wọn ni àmì-ẹ̀yẹ ewì Ẹgbẹ́ àwọn Òǹkọ̀wé Orílẹ̀èdè Nàìjíríà (Association of Nigerian Authors -  ANA), Àmì - Ẹyẹ Ewì Commonwealth, Àmì ẹ̀yẹ ewì Tchicaya U Tam'si àti àmì ẹ̀yẹ ewì ANA tòun ti iléeṣẹ́ Cadbury lẹ́ẹ̀mejì. Ní ọdún 1991, Ọ̀sundare di akéwì Adúláwọ̀ onígẹ̀ẹ́sì àkọ́kọ́ láti gba àmì ẹ̀yẹ NOMA, bákan náà ló gba àmì ẹ̀yẹ Fonlon Nichols fún iṣẹ́ takuntakun àti ipa ribiribi rẹ̀ sí ìjàfẹ́tọ̀ọ́ ọmọnìyàn ní ilẹ̀ Áfíríkà. Ní ọdún 2014, wọ́n gbà á wọlé sí National Order of Merit  tíì ṣe ẹ̀yẹ tó ga jù ní Orílẹ̀èdè rẹ̀ fún ìmọ̀ tó tayọ àti ìseyorí àtinúdá. Ọ̀jọ̀gbọ́n afẹ̀yìntì tí ó tayọ ní Ọ̀sundare ní Yunifásítì ti Ìlú New Orleans Ebí àti Èkó. Ẹbí àti Èkọ́:Ọ̀sundare gba oyè ẹ̀kọ́ BA. nínú Èdè Gẹ̀ẹ́sì ní Yunifásítì ti Ìlú Ìbàdàn, Oyè MA ni Yunifasiti Ìlú Leeds and Oyè Ph.D ní Yunifásítì ìlú Canada. Ó jẹ olórí ẹ̀ka Gẹ̀ẹ́sì ní Yunifásítì ti Ìbàdàn ní ọdún 1993 sí 1997. Ó di Ọ̀jọ̀gbọ́n Èdè Gẹ̀ẹ́sì ní Yunifásítì New Orleans ní ọdún 1997. Ọsundare ní ìyàwó àti ọmọ mẹ́ta tí wọ́n ṣì ń gbè ni Orílẹ̀èdè Nàìjíríà. Àwọn àmì ẹ̀yẹ. First Prize, Western State of Nigeria Poetry Competition (1968)[11] 1981 Major Book Prize and Letter of Commendation, BBC Poetry Competition (1981)[12] Honorable Mention, Noma Award for Publishing in Africa (1986)[13] Honorable Mention, Noma Award for Publishing in Africa (1989)[14] Association of Nigerian Authors (ANA) Poetry Prize (1986)[citation needed] Joint-Winner, Overall Commonwealth Poetry Prize (1986)[15] Kwanza Award (1991)[16] Noma Award for Publishing in Africa (the first Anglophone African poet to receive the award) (1991)[17] Cadbury/ANA Poetry Prize (Nigeria’s highest poetry prize). Also won the maiden edition in 1989 (1994)[18] Fonlon/Nichols Prize for "Excellence in Literary Creativity Combined with Significant Contributions to Human Rights in Africa"; African Literature Association (ALA)’s most distinguished award) (1998)[19] The Spectrum Books Award to The Eye of the Earth as “One of Nigeria’s Best 25 Books in the Last 25 Years” (2004)[20] The Tchicaya U Tam'si Prize for African Poetry (regarded as Africa's highest poetry prize) (2008)[21][22] Nigerian National Order of Merit Award (Nigeria's highest award for academic excellence) (2014)[23][24] Àkójọ pò isẹ́ rẹ̀. Songs from the Marketplace (1983)- Village Voices (1984)- The Eye of the Earth (1986, winner of a Commonwealth Poetry Prize and the poetry prize of the Association of Nigerian Authors)-[25] Moonsongs (1988)- Songs of the Season (1999)- Waiting Laughters (1990, winner of the Noma Award)-[26] Selected Poems (1992)- Midlife (1993)- Thread in the Loom: Essays on African Literature and Culture (2002)- The Word is an Egg (2002)- The State Visit (2002, play)- Pages from the Book of the Sun: New and Selected Poems (2002)- Early Birds (2004)- Two Plays (2005)- The Emerging Perspectives on Niyi Osundare (2003)- Not My Business (2005)- Tender Moments:Love Poems (2006)- City Without People: The Katrina Poems (2011)- Random Blues (2011)-
Niyi Osundare
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=16986
16986
Helen Ovbiagele Helen Ovbiagele je olukowe omo ile Naijiria.
Helen Ovbiagele
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=16987
16987
Sola Osofisan Sola Osofisan je olukowe omo ile Naijiria.
Sola Osofisan
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=16988
16988
Zulu Sofola Nwazuluwa Onuekwuke "Zulu" Sofola je olukowe omo ile Naijiria.
Zulu Sofola
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=16989
16989
Bode Sowande Bode Sowande je olukowe omo ile Naijiria.
Bode Sowande
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=16990
16990
Ken Wiwa Ken Wiwa je olukowe omo ile Naijiria. Ken je omo Ken Saro-Wiwa.
Ken Wiwa
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=16991
16991
Molara Wood Molara Wood je olukowe omo ile Naijiria.
Molara Wood
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=16992
16992
Abdullahi Sarki Mukhtar Abdullahi Sarki Mukhtar je oloselu omo ile Naijiria ati Gomina Ipinle Kaduna ati Ipinle Katsina tele.
Abdullahi Sarki Mukhtar
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=16995
16995
Akojo awon Gomina Ipinle Katsina
Akojo awon Gomina Ipinle Katsina
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=16996
16996
Àkòjọ àwọn Gómìnà Ìpínlẹ̀ Kàtsínà
Àkòjọ àwọn Gómìnà Ìpínlẹ̀ Kàtsínà
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=16997
16997
List of Governors of Katsina State
List of Governors of Katsina State
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=16998
16998
Àkójọ àwọn Gómìnà Ìpínlẹ̀ Kàdúná <onlyinclude>Atojo awon alamojuto ati awon Gomina Ipinle Kaduna. Ipinle Kaduna je didasile ni 27 May 1967 bi North Central State o si je titunsoloruko ni 17 Mar 1976 bi Ipinle Kaduna. </onlyinclude>
Àkójọ àwọn Gómìnà Ìpínlẹ̀ Kàdúná
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=16999
16999
List of Governors of Kaduna State
List of Governors of Kaduna State
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=17000
17000
Lawrence Onoja Lawrence Onoja jẹ́ ọmọ ilẹ̀ Nàìjíríà àti Gómìnà awon Ipinle Plateau ati Katsina tẹ́lẹ̀.
Lawrence Onoja
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=17001
17001
John Madaki John Madaki jẹ́ ọmọ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà àti Gómìnà Ìpínlẹ̀ Katsina nígbà kan rí. A yàn án sípò ní oṣù Kejìlá ọdún 1989 lásìkò ìjọba ológun tí Ààrẹ Ibrahim Babangida. Saidu Barda ló jẹ́ lẹ́yìn rẹ̀ lásìkò ìjọba alágbádá ni oṣù kìíní ọdún 1992.
John Madaki
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=17002
17002
Saidu Barda Saidu Barda jẹ́ ọmọ ilẹ̀ Nàìjíríà àti Gómìnà Ipinle Katsina tẹ́lẹ̀.
Saidu Barda
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=17003
17003
Emmanuel Acholonu Emmanuel Acholonu jẹ́ ọmọ ilẹ̀ Nàìjíríà àti Gómìnà Ipinle Katsina tẹ́lẹ̀.
Emmanuel Acholonu
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=17004
17004
Samaila Chama
Samaila Chama
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=17005
17005
Joseph Akaagerger Joseph Akaagerger jẹ́ ọmọ ilẹ̀ Nàìjíríà àti Gómìnà Ipinle Katsina tẹ́lẹ̀.
Joseph Akaagerger
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=17010
17010
List of Governors of Oyo State
List of Governors of Oyo State
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=17011
17011
Oládayọ̀ Pópóọlá Ogagun Agba Oládayọ̀ Pópóọlá (26 Osu Keji 1944) jẹ́ ọmọ ilẹ̀ Nàìjíríà àti Gómìnà Ológun Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ tẹ́lẹ̀.
Oládayọ̀ Pópóọlá
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=17012
17012
Tunji Olurin Adetunji Idowu Olurin (ojoibi 3 Osu Kejila 1944) jẹ́ ọmọ ilẹ̀ Nàìjíríà àti Gómìnà Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ tẹ́lẹ̀.
Tunji Olurin
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=17013
17013
Victor Omololu Olunloyo Victor Omololu Olunloyo (tí a bí ní ọjọ́ kẹrìnlá oṣù kẹrin ọdún 1935) jẹ́ onímọ̀ Mati tí ó di Gómìnà ìpínlẹ̀ Oyo, Nàìjíríà ní oṣù Kẹ̀wá ọdún 1983, ó di ipò náà mú fún ìgbà díẹ̀ kí ìjọba ológun Muhammadu Buhari tó gba ìjọba ní oṣù Kejìlá ọdún 1983. Ó padà darapọ̀ ẹgbẹ́ òsèlú People's Democratic Party (PDP) ní Ìpínlẹ̀ Oyo.
Victor Omololu Olunloyo
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=17014
17014
Rasheed Ladoja Rasheed Ladoja jẹ́ ọmọ ilẹ̀ Nàìjíríà àti Gómìnà Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ tẹ́lẹ̀.
Rasheed Ladoja
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=17015
17015
Paul Tarfa Paul Tarfa jẹ́ ọmọ ilẹ̀ Nàìjíríà àti Gómìnà Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ tẹ́lẹ̀.
Paul Tarfa
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=17016
17016
David Jemibewon David Medaese Jemibewon jẹ́ ọmọ ilẹ̀ Nàìjíríà àti Gómìnà Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ tẹ́lẹ̀.
David Jemibewon
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=17017
17017
Sasaenia Oresanya Adedeji Sasaenia Oresanya jẹ́ ọmọ ilẹ̀ Nàìjíríà àti Gómìnà Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ tẹ́lẹ̀.
Sasaenia Oresanya
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=17018
17018
Abdulkareem Adisa Abdulkareem Adisa (1949 - 25 February 2005) jẹ́ ọmọ ilẹ̀ Nàìjíríà àti Gómìnà Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ tẹ́lẹ̀.
Abdulkareem Adisa
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=17019
17019
Kolapo Ishola Kolapo Olawuyi Ishola jẹ́ ọmọ ilẹ̀ Nàìjíríà àti Gómìnà Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ tẹ́lẹ̀.
Kolapo Ishola
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=17020
17020
Adetoye Oyetola Sode Adetoye Oyetola Sode jẹ́ ọmọ ilẹ̀ Nàìjíríà àti Gómìnà Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ tẹ́lẹ̀.
Adetoye Oyetola Sode
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=17021
17021
Chinyere Ike Nwosu Chinyere Ike Nwosu jẹ́ ọmọ ologun omo orilẹ̀-ede Nàìjíríà to tifeyinti àti Gómìnà awon ipinle Abia ati Oyo tẹ́lẹ̀.
Chinyere Ike Nwosu
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=17022
17022
Ahmed Usman Ahmed Usman (1951-2021) jẹ́ ọmọ ilẹ̀ Nàìjíríà àti Gómìnà Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ tẹ́lẹ̀.
Ahmed Usman
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=17023
17023
Amen Edore Oyakhire Amen Edore Oyakhire jẹ́ ọmọ ilẹ̀ Nàìjíríà àti Gómìnà Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ tẹ́lẹ̀.
Amen Edore Oyakhire
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=17024
17024
Lam Adesina Lamidi Onaolapo Adesina (20 January 1939 – 11 November 2012) jẹ́ oloselu ọmọ ilẹ̀ Nàìjíríà àti Gómìnà Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ tẹ́lẹ̀.
Lam Adesina
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=17028
17028
Àkójọ àwọn Gómìnà Ìpínlẹ̀ Èkó <ns>0</ns> <revision> <parentid>539272</parentid> <timestamp>2023-09-25T08:36:36Z</timestamp> <contributor> <username>InternetArchiveBot</username> </contributor> <comment>Rescuing 1 sources and tagging 0 as dead.) #IABot (v2.0.9.5</comment> <model>wikitext</model> <format>text/x-wiki</format> <onlyinclude>Eyi ni àkójọ awọn alakoso ati awọn gomina ti Ipinle Eko. Lagos State was formed in 1967-05-27 from Colony province and Lagos federal territory. </onlyinclude>
Àkójọ àwọn Gómìnà Ìpínlẹ̀ Èkó
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=17030
17030
List of Governors of Lagos State
List of Governors of Lagos State
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=17032
17032
Ipinle Eko
Ipinle Eko
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=17035
17035
Local Government Areas in Nigeria
Local Government Areas in Nigeria
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=17036
17036
Mobolaji Johnson Mobọ́lájí Ohofunso Johnson jẹ́ ọmọ ilẹ̀ Nàìjíríà àti Gómìnà Ìpínlẹ̀ Èkó tẹ́lẹ̀.
Mobolaji Johnson
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=17037
17037
Adekunle Lawal Adekunle Shamusideen Lawal jẹ́ ọmọ ilẹ̀ Nàìjíríà àti Gómìnà Ìpínlẹ̀ Èkó tẹ́lẹ̀.
Adekunle Lawal
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=17038
17038
Ndubuisi Kanu Ndubuisi Kanu (1943-2021) jẹ́ ọmọ ilẹ̀ Nàìjíríà àti Gómìnà Ìpínlẹ̀ Èkó tẹ́lẹ̀.
Ndubuisi Kanu
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=17039
17039
Ebitu Ukiwe Okoh Ebitu Ukiwe (ojoibi 26 Osu Kewa 1940) jẹ́ ọmọ ologun ilẹ̀ Nàìjíríà totifeyinti ati Igbakeji Aare ile Naijiria àti Gómìnà tẹ́lẹ̀ fun Ìpínlẹ̀ Èkó ati Ipinle Niger.
Ebitu Ukiwe
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=17040
17040
Lateef Jakande Lateef Kayode Jakande (ọjọ́ìbí 23 July 1929-2021) jẹ́ ọmọ ilẹ̀ Nàìjíríà àti Gómìnà Ìpínlẹ̀ Èkó tẹ́lẹ̀ ati alákósó ètò iṣẹ abẹ́lé lábẹ́ ìjọba Sani Abacha.
Lateef Jakande
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=17041
17041
Gbolahan Mudasiru Gbolahan Mudasiru(eni ti a bi ni 18 October 1945 ti o si fayesile ni 23 September 2003) jẹ́ ọmọ ilẹ̀ Nàìjíríà àti Gómìnà Ìpínlẹ̀ Èkó tẹ́lẹ̀. O jé Gomina ipinle Èkó laarin Osu kinni odun 1984 si osù kejo odun 1986 nígba isejoba ologun Muhammadu Buhari àti Ibrahim Babangida.
Gbolahan Mudasiru
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=17042
17042
Mike Akhigbe Mike Akhigbe jẹ́ ọmọ ilẹ̀ Nàìjíríà ati Igbakeji Aare ile Naijiria àti Gómìnà Ìpínlẹ̀ Èkó tẹ́lẹ̀.
Mike Akhigbe
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=17043
17043
Raji Rasaki Ogagun Raji Alagbe Rasaki (ojoibi January 7, 1947) jẹ́ ọmọ ologun toti feyinti ara orile-ede Nàìjíríà àti Gómìnà Ipinle Eko, Ondo ati Ogun tẹ́lẹ̀.
Raji Rasaki
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=17044
17044
Michael Otedola Michael Otedola jẹ́ ọmọ ilẹ̀ Nàìjíríà àti Gómìnà Ìpínlẹ̀ Èkó tẹ́lẹ̀.
Michael Otedola
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=17045
17045
Buba Marwa Mohammed Buba Marwa (ojoibi September 9, 1953) jẹ́ ọmọ ilẹ̀ Nàìjíríà àti Gómìnà awon Ipinle Borno ati Eko tẹ́lẹ̀.
Buba Marwa
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=17048
17048
Àkójọ àwọn orúkọ àlàjẹ́ Ìpínlẹ̀ Nàìjíríà Tabili isale yi safihan akojo awon oruko alaje awon ipinle Naijiria.
Àkójọ àwọn orúkọ àlàjẹ́ Ìpínlẹ̀ Nàìjíríà
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=17049
17049
List of Nigerian state nicknames
List of Nigerian state nicknames
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=17050
17050
Adamawa State
Adamawa State
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=17051
17051
Akwa Ibom State University of Science and Technology 'Akwa Ibom State University of Science and Technology ni yunifásítì ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.
Akwa Ibom State University of Science and Technology
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=17052
17052
ABTI - American University of Nigeria ABTI - American University of Nigeria ni yunifásítì taladani ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.
ABTI - American University of Nigeria
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=17053
17053
Yunifásítì Ìpínlẹ̀ Adámáwá 'Yunifásítì Ìpínlẹ̀ Adámáwá jẹ́ ọ̀kan lára àwọn yunifásítì ìjọba ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.
Yunifásítì Ìpínlẹ̀ Adámáwá
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=17054
17054
Yunifásítì Ambrose Alli Yunifásítì Ambrose Alli ni yunifásítì ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.
Yunifásítì Ambrose Alli
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=17055
17055
Yunifásítì Ìpínlẹ̀ Anámbra Yunifásítì Ìpínlẹ̀ Anámbra ni yunifásítì ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.
Yunifásítì Ìpínlẹ̀ Anámbra
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=17056
17056
Yunifásítì Ìpínlẹ̀ Bẹ́núé Yunifásítì Ìpínlẹ̀ Bẹ́núé ni yunifásítì ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.
Yunifásítì Ìpínlẹ̀ Bẹ́núé
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=17057
17057
Cross River State University of Technology Yunifásítì ti Ìpínlẹ̀ Cross River tí a tún mọ̀ sí UNICROSS jẹ́ ilé-ẹ̀kọ́ gíga ti ìjọba tí ó ní àwọn ilé-ẹ̀kọ́ gíga mẹ́rin tí ó tàn káàkiri àwọn ìjọba ìbílẹ̀ mẹ́rin ti ìpínlẹ̀ náà. Ilé-ẹ̀kọ́ gíga tí a mọ̀ tẹ́lẹ̀ sí Cross River University of Technology (CRUTECH). Ó tún orúkọ rẹ̀ ní ní oṣù kejì ọdún 2021 nípasẹ̀ àbádòfin tí ó kọjá ní Ilé-ìgbìmọ̀ aṣòfin Ìpínlẹ̀ Cross River èyítí Gómìnà Ìpínlẹ̀ náà, Benedict Ayade fọwọ́sí lẹ́hìn náà. Ìyípadà ti orúkọ ilé-ẹ̀kọ́ gíga ni láti jẹ́ kí iṣẹ́ fásítì ṣiṣẹ́ bí Ilé-ẹ̀kọ́ gíga ti àṣà, èyítí ó pèsè àyè láti fúnni ní àwọn iṣẹ́ ìkẹ́kọ̀ọ́ díẹ̀ síi dípò ìdojúkọ́ lórí àwọn iṣẹ́ ìkẹ́kọ̀ọ́ ti ìmọ̀-ẹ̀rọ. Ilé-ẹ̀kọ́ gíga gba orúkọ abínibí ti ìpínlẹ̀ náà padà ti Ilé-ẹ̀kọ́ gíga ti Ìpínlẹ̀ Cross River, Uyo ní báyìí Yunifásítì ti Uyo, Ìpínlẹ̀ Akwa Ibom, Nàìjíríà títí di ọjọ́ kìíní oṣù kẹ́wàá ọdún 1991 nígbà tí ìjọba àpapọ̀ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà da Fásítì ti Uyo sílẹ̀ gẹ́gẹ́ bí Ilé-ẹ̀kọ́ gíga àpapọ̀ lẹ́hìn ìpínyà ti ìlà Akwa Ibom láti Ìpínlẹ̀ Cross River ní ọdún 1987. Ilé-ẹ̀kọ́ gíga ti Uyo jogún àwọn ọmọ ilé-ìwé, òṣìṣẹ́, àwọn ètò ẹ̀kọ́ àti gbogbo àwọn ohun èlò ti Ilé-ẹ̀kọ́ gíga ti Ìpínlẹ̀ Cross River nígbà náà ti ìṣètò nípasẹ̀ Ìpínlẹ̀ Cross River ní ọdún 1983.
Cross River State University of Technology
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=17058
17058
Delta State University Abraka-Nigeria Delta State University Abraka-Nigeria ni yunifásítì ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.
Delta State University Abraka-Nigeria
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=17059
17059
Yunifásítì Ìpínlẹ̀ Ẹ̀bọ́nyì Yunifásítì Ìpínlẹ̀ Ẹ̀bọ́nyì jẹ́ ọ̀kan lára àwọn yunifásítì ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.
Yunifásítì Ìpínlẹ̀ Ẹ̀bọ́nyì
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=17060
17060
Enugu State University of Science and Technology Enugu State University of Science and Technology ni yunifásítì ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.
Enugu State University of Science and Technology
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=17061
17061
Yunifásítì Tẹknọ́lọ́jì Àpapọ̀ ilú Àkúrẹ́ Yunifásítì Tẹknọ́lọ́jì Àpapọ̀ ilú Àkúrẹ́ ni yunifásítì ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà. Ni óṣu April, ọdun 2023, Ọgbẹni Charles Adẹlẹyẹ to jẹ ọmọ ọdun mẹrin din lọgọta ni a fi jẹ registrar tuntun fun ilè iwè giga naa ti Ọgbẹni Robert Awoyẹmi to jẹ ọmọ ọdun mẹta leelaadọta jẹ alakoso yara ikawe tuntun ta ṣẹṣẹ yan.
Yunifásítì Tẹknọ́lọ́jì Àpapọ̀ ilú Àkúrẹ́
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=17064
17064
Yunifásítì Ìpínlẹ̀ Gòmbè Yunifásítì Ìpínlẹ̀ Gòmbè jẹ́ ọ̀kan lára àwọn yunifásítì ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.
Yunifásítì Ìpínlẹ̀ Gòmbè
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=17065
17065
Yunifásítì Ìpínlẹ̀ Ímò Yunifásítì Ìpínlẹ̀ Ímò ni yunifásítì ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.
Yunifásítì Ìpínlẹ̀ Ímò
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=17066
17066
Yunifasifi ti Ladoke Akintola ti Imọ-ẹrọ Yunifasifi ti Ladoke Akintola ti Imọ-ẹrọ ni yunifásítì to wa ni ilu Ogbomọshọ ipinlẹ Ọyọ, orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.
Yunifasifi ti Ladoke Akintola ti Imọ-ẹrọ
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=17067
17067
Yunifásítì Ìpínlẹ̀ Èkó Yunifásítì Ìpínlẹ̀ Èkó ti a tun mọ si LASU, wa ni Ojo, ilu kan ni Ipinle Eko, Nigeria. Ile-ẹkọ giga ti dasilẹ ni ọdun 1983 nipasẹ ofin ti o fun laaye ni Ipinle Eko, fun ilosiwaju ti ẹkọ ati idasile didara ẹkọ giga; gbolohun ọrọ rẹ jẹ Fun Otitọ ati Iṣẹ.
Yunifásítì Ìpínlẹ̀ Èkó
https://yo.wikipedia.org/wiki?curid=17068
17068
Federal Polytechnic Birnin Kebbi Federal Polytechnic Birnin Kebbi ni yunifásítì ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.
Federal Polytechnic Birnin Kebbi