10494#0 ọdun wo ni wọn pa funsho william? 10773#0 osu meloo ni oyun ma n lo nínú ikun obinrin ? 10981#0 Ki ni oruko ibilẹ ilu Port Harcourt? 11043#0 ipinlẹ wo ni gbenga Daniel ti jẹ gomina? 11172#0 Ki ni olu-ilu orile-ede Burkina-Faso? 11296#0 Ki ni oluilu Bangladesh? 11435#0 Odun wo ni Nwankwo Kanu da pọ mọ Arsenal? 11775#0 Ki ni orukọ iyawo Babatunde Fasola? 11810#0 Ki ni oluilu orile ede Bulgaria? 12525#0 Ki ni oluilu orile ede Hungari? 13297#0 ọmọ orílé ede wo ni Bill Gates ? 13310#0 kini oluilu orile-ede Paraguai? 13361#0 Ta ni o da ile iṣẹ Innoson silẹ? 13883#0 Orile ede wo ni Cape Town wa ? 13915#0 kí ni oluilu ipinle Akwa-Ibom? 14498#0 Iṣẹ wo ni Sunday Igboho n ṣe? 14783#0 Odun wo ni wọn pari ogun agbaye ikeji? 14826#0 ogagun wo lo ṣe aṣáájú àwọn ologun Biafra ni odun 1967? 14874#0 Orile ede wo ni ilu Boston wa? 15062#0 Ki ni oluilu ipinle akwa ibom? 15197#0 Iwe wo ni Ibn Battuta kọkọ kọ? 15241#0 Onimo mathematiki wo lo gbe Algebra jade? 15252#0 awọn ẹbun wo ni Roald Engelbregt gba ? 15265#0 Ta ni oba orile ede Bahrain? 15335#0 Orile ede wo ni wọn bí Kamaru Usman sí? 15367#0 ẹgbẹ olóṣèlú wo ni David Mark wa pẹlu? 15596#0 Omo orile ede wo ni Cheikh Diop? 15777#0 Ṣe orile-ede Bhutan wa ni Asia? 15787#0 Ki ni oluilu Burkina Faso? 15805#0 ọdun wo ni orile ede Kongo gba ominira? 15807#0 ipo wo ni Adolphe Muzito je labe ijoba Joseph Kabila? 15809#0 ki ni iye eeyan to wa ni orile-ede kroatia? 15882#0 obinrin alawọ dudu wo lo kọkọ yege idije Miss World? 15884#0 ọdun wo ni agbani darego yege idije Miss World? 15898#0 Ki ni wọn n pe ni Eurasia? 16001#0 kí ni olu-ilu orile-ede norway? 16007#0 Ipinle wo ni Ilu Gbongan wa? 16238#0 orile ede wo ni Ilu Madrid wa? 16281#0 Ta ni iyawo Bill Clinton? 16297#0 Èdè wo ni àwọn ará orile ede Nepal n sọ? 16373#0 Omo orile-ede wo ni onimo mathematiki Carl Friedrich? 16407#0 Odun wo ni Sultan Muhammadu Maccido ku? 16427#0 Odun wo ni won bi onisowo Efunroye Tinubu? 16770#0 Ki ni oruko bibi alawada Frank Donga? 16781#0 Ki ni oluilu ipinle Ondo? 16798#0 Odun wo ni Ekiti ati Ondo ya sọtọ? 16956#0 Tani Philip Efiong ja fun ni Ogun Biafra? 17024#0 Ipo oselu wo ni Lamidi Adesina di mu gege bi oloselu ? 17206#0 Omo ipinle wo ni Lateef Adedimeji? 17372#0 kí ni orúkọ ọba sultan ilu sókótó? 17539#0 kí ni olú ìlú ipinlẹ Rivers ? 17559#0 Ki ni olu-ilu ipinle Anambra? 17600#0 Ta ni Sultan Sokoto ni odun 2003? 18307#0 Ipinle wo ni Yunifasiti Olabisi Onabanjo wa? 18308#0 Odun wo ni Oladipo Diya je gomina ipinle Ogun l'asiko ijoba ologun? 18397#0 Odun wo ni Fidel Castro kuro lori aleefa? 18519#0 Orile ede wo ni odo Amazon wa? 18548#0 Orile-ede wo ni ilu Houston wa? 18560#0 Ta ni Aare orile-ede Amẹrika? 18642#0 kí ni oluilu orile ede Peru? 18667#0 Odun wo ni orile ede Mozambique gba ominira? 18668#0 ọdun wo ni orile-ede Mozambique gba ominira? 18809#0 Iru ounjẹ wo ni wọn ma n jẹ ni ipinle Akwa Ibom? 18859#0 Ilu wo ni won bi Serena Williams si? 18964#0 ẹgbẹ olóṣèlú wo ni Ibrahim Shekarau wa pẹlu? 19071#0 Ki ni oluilu ipinle kebbi? 19115#0 Ki ni oluilu ipinlẹ Niger? 19133#0 Odun wo ni Musilliu Haruna Ishola kọ soyoyo? 19661#0 Omo odun meloo ni Mike Tyson nigba to kọkọ gba oye heavyweight? 19971#0 Orile-ede wo ni ilu Dar es Salaam wa? 19977#0 Ise wo ni Benjamin Franklin ṣe? 20041#0 Awon orile ede wo lo yika Tanzania? 20338#0 Odun wo ni won bi onimo sayensi Thomas Edison? 20453#0 Ki ni asia orile-ede Morocco? 20573#0 Kí ni orúkọ ilé ìjọsìn David Oyedepo? 20647#0 Ibaṣepọ wo lo wa laarin Michael Jackson ati Janet Jackson ? 20692#0 Akowe wo lo kọ iwe Arrow of God? 20772#0 Odun wo ni Ogun Agbekọya bẹrẹ? 20782#0 Kí ni oluilu ipinle Jigawa? 21115#0 Kí ni oluilu orile-ede Macedonia? 21578#0 Olukowe wo lo kọ iwe Jagua Nana? 21666#0 Ọmọ ipinle wo ni Uche Jombo? 21915#0 Odun wo ni Ronald Reagan jẹ gomina California? 22043#0 Ki ni Iṣẹ igbakeji aarẹ? 22144#0 Ki ni oluilu orile ede Uganda? 22501#0 Orile ede wo ni ilu Boston wa? 22562#0 Se orile-ede Griisi dara? 22595#0 Ilu wo ni George Washington ṣe Aarẹ fun? 22677#0 Orile ede wo ni ilu Athens wa? 23142#0 Ki ni olu-ilu orile-ede Argentina? 23245#0 Awon eya wo lo tobi ju lọ ni orile-ede sierra leone? 23562#0 Omo orile ede wo ni Karl Marx? 23647#0 Kí ni oluilu orile-ede Switzerland? 25182#0 Kí ni orúkọ inagijẹ òṣèré Taiwo Hassan ? 25674#0 ọdún wo ni asiwaju Bola Tinubu kọkọ jẹ gomina ipinle Eko? 26004#0 Odun wo ni Augusto Pinochet fi aye silẹ? 26186#0 awọn orile ede wo ni àwọn komunisti pọ sí jù? 26190#0 Ara Ilu wo ni Rosa Luuxemburg? 26237#0 ọdún wo ni orile-ede Nàìjíríà di republiki? 26401#0 Ọdún wo ni Joseph Stalin fi ayé silẹ? 2749#0 Ki ni oluilu Andorra? 28166#0 egbe oṣelu wo ni Barack Obama wa pẹlu? 28630#0 Ojo melo lo wa ninu oṣu Februrari? 29343#0 Ise wo ni Ludwig Van Beethoven ṣe? 30023#0 Ile-ise wo ni Ezra Olubi da sile? 30081#0 Olorin wo lo kọ orin "African Queen"? 30366#0 Kí ni orúkọ inagijẹ onisowo orin Sean Combs ? 30369#0 Awọn ẹbun wo ni Jack Nicholson ti gba fún eré ṣíṣe? 31331#0 Pilaneeti wo lo tobi ju ̀lọ? 3171#0 Ki ni olu ilu orile-ede Cameroon? 32958#0 Ọdun wo ni wọn pari Ogun Biafra? 33282#0 Ki ni itumọ Homo Sapien? 3346#0 Ki ni iyatọ laarin "odd nomba" ati "even nomba"? 33857#0 Omo orile ede wo ni Maria Sharapova? 33976#0 Odun wo ni Joseph Stalin s'alaisi? 33997#0 ọdun wo ni wọn da orile-ede Amerika silẹ? 34105#0 ipò wo ni Teslim Elias jẹ ni International court of justice? 34138#0 Ki ni o fa iku Giordano Bruno? 35546#0 Ise wo ni Whoopi Goldberg n se? 35579#0 Ọdún wo ni Ronald Reagan jẹ ààrẹ Orile-ede Amẹrika? 35617#0 Ilu wo ni wọn bi Colin Powell si? 36817#0 Odun wo ni Bola Tinubu di Seneto? 36873#0 Iru orin wo ni Segun Adewale n kọ? 36889#0 iru orin wo ni Majek Fashek kọ? 36898#0 ile iṣẹ wo ni Peter Thiel da silẹ? 36940#0 Agbegbe wo ni Senator Abaribe n ṣe aṣoju fún? 37099#0 Ki ni Nnamdi Kanu n ja fun? 37133#0 Ki ni idi ti Suka Dimka ṣe fẹ pa Murtala? 37197#0 orile ede wo ni ilu San Francisco wa? 37479#0 Odun wo ni oṣere Moses Olaiya fi aiye silẹ? 37653#0 ọdun wo ni George washington ṣ'alaisi? 37671#0 Odun wo ni George Bush di Aare orile-ede Amerika? 37738#0 ọdún wo ni Colin Powell fi ayé silẹ? 38162#0 Agbegbe ijjọba Ibilẹ wo ni Desmond Elliot n ṣe aṣoju fun? 38221#0 Ki ni oluilu orile-ede Belarusi? 42261#0 Planeti meloo lo wa? 47009#0 Odun wo ni awon onimosayensi se awari 141 Lumen? 5126#0 Ki ni orukọ ọọni Ile Ifẹ? 5223#0 Ọdún wo ni Adesoji Aderemi jẹ Ọọni Ile Ifẹ? 53718#0 Odun wo ni Chang Myon je Minisita orile-ede Korea 53740#0 Kí ni oluilu orile-ede Kenya? 53890#0 ẹgbẹ oloṣelu wo ni Corey Booker wa pẹlu? 5392#0 Odun wo ni Olagunsoye Oyinlola di gomina Osun? 53994#0 Ta ni aare Egypti ni ọdun 2010? 54187#0 Kí ni orúkọ inagijẹ Andre Young ? 54188#0 Ki ni orukọ akọrin Curtis Jackson? 54270#0 Iṣẹ wo ni Rosa Parks ṣe? 54280#0 awọn Orile ede wo ni wọn ti n sọ Swahili? 54886#0 ẹkọ wo ni a le mu lo lati aye Jésù kristi? 55834#0 Odun wo ni Nelson Mandela kuro ni ẹwọn? 58528#0 Iṣẹ wo ni Margaret Etim n ṣe? 58529#0 Ta ni Aarẹ orile-ede Russia? 58653#0 Akorin wo lo kọ "Billie Jean" ? 59313#0 Odun wo ni Sloane Stephens yege US open? 59530#0 Odun wo ni Gloria Macapagal di aare orile ede Fillipines? 59753#0 iru metali wo ni aluminiomu? 59915#0 ọdun wo Saddam Hussein ṣe alaisi? 59947#0 Ati orile ede wo ni Reggae ti wa? 60031#0 Iru orin wo ni John Lennon kọ? 60042#0 Awon orile ede wo lo sunmo Rọṣia? 60106#0 Ki ni orukọ inagije Charles Olumọ? 60184#0 Ilu wo ni wọn bi Serena Williams si? 60571#0 Odun wo ni won bi onimo sayensi Isaac Newton? 60777#0 ọmọ ìlú wo ni Linda Ejiofor? 61172#0 Ki ni inagijẹ Dwayne Carter ? 61423#0 ọdun wo ni wọn bi aarẹ Muhammadu Buhari? 61829#0 ki ni o ma n fa arun Onchocerciasis? 61835#0 Odun wo ni Cassius Clay yi oruko si Muhammed Ali? 61882#0 Orile ede wo ni Tenerife wa? 62015#0 kí ni o ma n fa arun ọpọlọ? 62016#0 Oogun wo ni eeyan le lo lati fi pa kokoro? 62175#0 kí ni o ma n fa arun ọpọlọ? 62192#0 Ẹbun fiimu mélòó ni Stephen Spielberg ti gba ? 62295#0 idile wo ni Awujalẹ Sikiru Adetona ti wá? 62300#0 ọdun wo ni wọn da ẹgbẹ PDP silẹ? 62444#0 Odun wo ni Lateef Adedimeji bẹrẹ si ṣe fiimu? 62453#0 Awon aami wo lo ma n han wipe obinrin ti ni oyun? 65763#0 kí ni oluilu orile-ede Gambia ? 65784#0 Awo meloo ni Sikiru Ayinde Barrister ṣe ki o to ku? 65842#0 ọdún wo ni akorin Victor Olaiya ṣ'alaisi 66100#0 Ki ni oruko ile-ise tI Sean Combs da sile? 66113#0 Ipinle wo ni Aliyu Wamakko ti jẹ gomina? 66437#0 ọmọ ilu wo ni Lawrence Anini? 66876#0 Awon tira wo ni Sheik Adam Al Ilory kọ? 66945#0 ọdún wo ni wọn pa Tafawa Balewa? 67007#0 bawo ni moremi ṣe tú àṣírí àwọn ará Igbo? 67317#0 Ta ni ẹni to kọ fiimu Ovy's voice? 67362#0 Odun wo ni 9ice gbe awo Gongo Aso jade? 67416#0 Ati ibo ni Aṣọ Ofi ti wa? 67527#0 Yunifasiti wo ni Funsho Williams ti kàwé? 67557#0 ile-ise wo ni Tara Fela-Durotoye da silẹ? 67562#0 Ọdún wo ni Wahab Folawiyo fi aiyé silẹ? 67610#0 Ki ni oluilu orile-ede Kenya? 67616#0 ọjọ wo ni Valentine bọ si? 67649#0 Odun wo ni won da OGBC silẹ? 67675#0 Awọn orile ede wo ni wọn ti n sọ Urdu? 67686#0 Awon irin ise wo ni akorin Prince lo? 67688#0 ọdún wo ni akọrin Fatai Rolling Dollar ṣ'àláìsí? 67760#0 Ilu wo ni won bi Immanuella Samueli si? 67764#0 Ọdún wo ni Chioma Ajunwa gba ẹbun ni ìdíje òlímpíkì? 67775#0 Ki lo pa Samuel Okwaraji? 67786#0 Odun wo ni Gbenga Daniel je gomina ipinlẹ Ogun? 67886#0 Ta ni ọba awọn ogu ni Badagry? 67907#0 Ki ni oruko iyawo Odunlade Adekola? 67942#0 Ipò wo ni Surajudeen Ajibola jẹ ni ipinlẹ Ọsun ? 67949#0 Ọdún wo ni Haruna Ìṣọ̀lá fi aiyé silẹ? 67956#0 yunifasiti wo ni gomina Dapo Abiodun ti kàwé? 67961#0 Odun wo ni olorin tupac shakur s'alaisi? 67991#0 ipo wo ni Robert Adeyinka je ni Western Region 68015#0 kí ni orúkọ ìyàwó Yemi Osinbajo? 68024#0 Ta ni Akran ilu Badagry? 68035#0 ilé iṣẹ wo ni Tony Elumelu da silẹ? 68047#0 Ọdún wo ni George Weah di ààrẹ orile ede Liberia? 68053#0 ọdún wo ni Bukky Wright bẹrẹ sí ṣe eré itage? 68058#0 Ta ni Baba Kunle Afolayan? 68059#0 ibaṣepọ wo lo wa laarin Gabriel ati Kunle Afolayan? 68234#0 Odun wo ni won da ile ifowoppamo Wema silẹ? 68240#0 Awon ile-ise wo ni Mark Zuckerberg da sile? 68242#0 Àwọn Gómìnà wo lo da ẹgbẹ amọtẹkun silẹ? 68250#0 awọn wo lo ko samuel crowther l'ẹ́rú? 68301#0 Kí ni èèyàn lè fi ata ṣọ̀mbọ̀ sè? 68376#0 Ipinle wo ni Samuel Ortom ti je gomina? 68427#0 kí ni olúìlú ìpínlẹ̀ Abia? 68435#0 Orile ede wo ni ilu Phoenix wa ? 68664#0 Ki ni o fa iku Tolulope Arotile? 68728#0 nibo ni abule faransé wa ni Badagry? 68737#0 Ki ni awon aami wipe eeyan ti ni ni arun Coronavirus? 68841#0 Ta ni oludari NCDC? 68861#0 Ọjọ meloo lo wa ninu oṣu Februrari? 68882#0 Odun wo ni Kemi Adetiba gbe fiimu King of Boys jade? 69261#0 Ile iroyin wo ni Aisha Falode ba ṣiṣẹ? 69404#0 Ki ni orukọ abisọ alakitiyan Malik El Shabazz? 69661#0 Ki ni orukọ abisọ Burna Boy? 69674#0 Ki ni a n pe ni pythagoras theorem ni Matimatiki? 69736#0 ati ilu wo ni COVID 19 ti kọkọ bẹrẹ? 69944#0 Ile-ise wo ni Bode Akindele da silẹ? 70088#0 olorin wo lo ko "African Queen" ? 70147#0 Fiimu wo ni Rahama Sadau ṣe pẹlu Ali Nuhu? 70174#0 ere mélòó ni òṣèré eniola ajao ti ṣe? 70219#0 Iṣẹ wo ni Sandra Ezekwesili ń ṣe? 70236#0 Odun wo ni Mike Bamiloye da Mount Zion sile? 70265#0 Oye wo ni fi Gani Adams jẹ? 70287#0 ere wo ni Bukky Ajayi kọkọ gbe jade? 70355#0 Ara ìlú wo ni Ààfáà Muyideen Bello? 70363#0 Ta ni ọkọ Thelma Okoduwa? 70419#0 Ipinle wo ni Yunifasiti Ahmadu Bello wa? 70433#0 Ise wo ni Margaret Etim n ṣe? 70450#0 Kí ni orúkọ inagijẹ òṣèré tí a mọ sí Taiwo Hassan? 70460#0 Ile-iwe ko giga ẹwo ni Yvonne Orji ti ka'we? 70493#0 Ipo wo ni won fi Kemi Adeosun si labe ijoba Muhammadu Buhari 70503#0 Ilu wo ni won bi Agnes Osazuwa si? 70557#0 Ede wo ni wọn sọ ni orile-ede Burkina? 70571#0 Omo ilu wo ni Mercy Johnson? 70576#0 Ipinle wo ni Ibrahim Shekarau ti jẹ gomina? 70598#0 ọdún wo ni Ogun àdùbí bẹrẹ? 70614#0 Odun wo ni Chioma Ajunwa yege ni idije olympiiki? 70629#0 Fiimu meloo ni Ini Ikpe ti ṣe? 70633#0 ọdún wo ni akọwe Frances Welsing fi aiyé silẹ? 70656#0 Orile ede wo ni Marina Niava to wa? 70693#0 Ọdún wo ni Leopold Senghor di ààrẹ orile-ede Senegal? 70729#0 Ta ni o se oludari fiimu Mionga ki Obo? 70783#0 ọdún wo ni wọn bí Anọbi Muhammad? 70918#0 Ki ni orukọ inagije Temilade Openiyi? 70933#0 Ẹgbẹ olóṣèlú wo ni Adeniran Ogunsanya bá ṣe? 70964#0 Odun wo ni Akiwunmi Ambode jẹ gomina ipinlẹ Eko? 70974#0 Ta ni o da ile iṣẹ Mainframe silẹ? 70993#0 ipò ìjọba wo ni Femi Adesina wa labẹ ijoba Aare Buhari? 70994#0 Orile ede wo lo yege idije World Cup ti 2006? 71068#0 Awọn nkan wo ni wọn fi n ṣe Baba Ghanoush? 71092#0 Awo wo ni Temi Dee kọkọ gbé jade? 71178#0 Ipinle wo ni Ayodele Fayọse ti ṣe gomina? 71200#0 Ọdún wo ni Ezra Olubi da ilé iṣẹ Paystack silẹ? 71202#0 Iṣẹ wo ni Tiwalola Olanubi n ṣe? 71220#0 yunifasiti wo ni denrele ti kàwé? 71252#0 ki ni anfani ere idaraya? 71280#0 Ta ni ọkọ Naa Ashorkor? 71282#0 Ọdún wo ni ọgbẹni Rauf Aregbesola jẹ gomina ipinlẹ Ọsun? 71307#0 ọdún wo ni Michael Jackson gbe awo Thriller jáde? 71352#0 konsonanti mélòó ló wà nínú èdè Yorùbá? 71424#0 Odun wo ni Oluwaseun Osewa da Nairaland silẹ? 71511#0 oṣu wo ni odun 1999 ni Olusegun Obasanajo di Aarẹ orile ede Naijiria? 71529#0 Odun wo ni Vivica Fox bẹrẹ si ṣe ere itage? 71554#0 Odun wo ni Facebook ra Whatsapp? 71569#0 Odun wo ni arun coronavirus bẹrẹ? 7183#0 orile ede wo ni odo mississipi wa? 7208#0 Ọjọ mélòó ló wà nínú oṣù Dìsẹ́mbà? 7523#0 Kí ni orúkọ abisọ Kwame Ture? 8837#0 ẹgbẹ oloṣelu wo ni Boris Johnson wa pẹlu?