10020#0 Odun wo ni wọn ṣe idije Olympiiki akọkọ? 10118#0 Orile ede wo ni Washington DC wà? 11164#0 Ipa wo ni Benito Mussolini se ni Ogun World War 2? 11194#0 ẹgbẹ wo ni Huey Newton da silẹ? 11419#0 Ilu wo lo tobi ju lọ ni orile-ede Poland 11673#0 Ki ni oluiilu orile ede Japan? 12167#0 ọdún wo ẹlẹsẹ ti a mọ sí Dick Tiger ṣ'aláìsí? 12299#0 ilu wo lo tobi julọ ni orile-ede Mauritania? 13308#0 kí ni olú ìlú orile ede Puerto Rico? 13935#0 Awon orile ede wo ni won pe ni Balkani? 15096#0 Odun wo ni Andy Ruiz ati Anthony Joshua ja? 15124#0 ọmo orile ede wo ni John Locke? 15131#0 ọjọ meloo lo wa ninu oṣu february? 15329#0 Ọdún wo ni Namadi Sambo jẹ Gomina ipinle Kaduna ? 15512#0 Awon orile ede wo lo yika Austria? 16114#0 oṣù wo ni keresimesi má ń bọ́ sí? 16348#0 Egbe oloselu wo ni Boris Johnson wa pẹlu? 16384#0 ọdún wo ni Emomali Rahmon di ààrẹ Orile ede Tajikistan? 17311#0 ipinlẹ wo ni Isiala Ngwa wa ni Nàìjíríà? 17552#0 Ipinle wo ni ilu Orlu wa? 18031#0 Odun wo ni won da egbe World Health Organization silẹ? 18270#0 Orile ede wo ni San Marino wa? 19496#0 Ta ni Aarẹ orile ede Ivory Coast? 20231#0 Odun wo ni Augusto Pinochet je aare orile-ede Chile? 20613#0 Odun wo ni Jolly nyame je gomina ipinle taraba? 20775#0 kí ni oluilu orile-ede griisi? 20961#0 Omo orile-ede wo ni osere Yvonne Nelson? 22786#0 Ọdún wo ni Pope John Paul s'alaisi? 23435#0 ọdun wo ni Julius Caesar ku? 23534#0 Odun wo ni King Leopold ṣ'alaisi? 23620#0 Ki ni oruko ṣọọsi Paul Adefarasin? 23625#0 Ki ni olu-ilu orile-ede Egypt? 24640#0 ọdun wo ni Pope John Paul ṣ'alaisi? 24860#0 Oṣù wo ni ọdún 1967 ni ogun Biafra bẹrẹ? 24913#0 Odun wo ni wọn da ẹgbẹ United Nations silẹ? 25355#0 Orukọ wo ni a n pe orile-ede Botswana ki wọn to yi pada? 2596#0 Ki ni oluilu orile ede Albania? 26086#0 Kí ni oluilu orile-ede Finland? 27070#0 Odun wo ni won bi Otto von bismarck? 27745#0 ọmọ orile ede wo ni Samuel Peters? 28208#0 ọdún wo ni wọn kọkọ bẹrẹ ẹbun Nobel ? 3017#0 Nibo ni Naijira ni Nok wa? 30269#0 ọdún wo ni alpha conde jẹ ààrẹ Orile ede guinea? 31034#0 Iwe meloo ni Mary Anne Evans kọ? 31099#0 Odun wo ni Adekunle Ajasin fi aiye silẹ? 3331#0 ọjọ meloo lo wa ninu oṣu August? 33551#0 Awon orile-ede wo lo sunmo Tunisia? 3545#0 Ọmọ ìlú wo ni òṣèré Genevieve Nnaji? 36841#0 Ile iṣẹ iroyin wo ni Funmi Iyanda ba ṣiṣẹ? 37663#0 Ẹlẹṣẹ wo ni a mọ si Cassius Clay? 37746#0 Ilu wo ni wọn bi Bobby Benson si? 38048#0 Ọdún wo ni Napoleon Bonaparte ṣ'alaisi? 38275#0 kí ni oluilu orile-ede Haiti? 4078#0 ṣe ipinle Ọṣun ni Ile Ife wa? 54948#0 ẹbun Grammy mélòó ni Mary J Blige ti gbà? 59455#0 ọdún wo ni Mariah Carey kọkọ gbé àwo jáde? 60238#0 Omo orile ede wo ni Li Lianjie? 60314#0 Ki ni orukọ ogbontarigi oṣere ti a mo si Baba Suwe ? 60391#0 Ki ni orukọ ile iṣẹ ti Dapo Abiodun da silẹ? 61267#0 Ilu wo lo tobi ju lọ ni orile ede Bulgaria? 62459#0 olorin wo lo kọ "Billie Jean" ? 62487#0 Ta ni ẹni tó dá Linux sílẹ̀? 62594#0 ọdún wo ni Bola Tinubu jẹ gomina Eko? 67530#0 Yunifasiti wo ni Dapo Abiodun ti ka'we? 67726#0 kí ni oluilu orile-ede South Sudan ? 67866#0 Kini oruko ṣọọsi ti David Oyedepo da silẹ? 67944#0 Ile-iwe eko giga wo ni Tam David West ti kawe? 68042#0 Ta ni ẹni tó ní ilé iṣẹ soundcity ? 68128#0 Iṣẹ wo ni Lizzy Anjorin ṣẹ? 68177#0 iru orin wo ni Fela Kuti kọ? 68257#0 Odun wo ni Frederick Fasheun ṣ'alaisi? 68382#0 Odun wo ni Aremu Gbadebo je Alake? 68412#0 Ta ni o da ile iṣẹ Daar Communications silẹ? 68449#0 Bawo ni awọn Hausa ṣe n ṣe Fura ti wọn? 68452#0 Ọdún wo ni wọn da ilé iṣẹ Facebook silẹ? 68729#0 Awon eya wo ni Ghana ni won sọ ede Akan 68921#0 Odun wo ni ogun Kiriji bẹrẹ? 69129#0 Ilu wo ni wọn bí Yvonne Nelson si ? 69146#0 Iṣẹ wo ni Aisha Buhari n ṣe?? 69209#0 Omo orile ede wo ni William Onyeabor? 69258#0 Ibasepo wo lo wa laarin Oluremi ati Bola Tinubu? 69260#0 ilé iṣẹ iroyin wo ni Eugenia Abu bá ṣiṣe? 69301#0 Akọwe wo lo kọ "Things fall apart"? 69308#0 ọdún wo ni oba rilwanu Akiolu di ọba eko? 69396#0 Odun wo ni Botswana gba ominira? 69434#0 Kí ni orúkọ ilé iṣẹ ti Alhaji Razaq Ọkọya da silẹ? 70116#0 Ilu wo ni Moshood Abiola Politekniki wa? 70124#0 ọdun wo ni orile-ede Naijiria gba ominira? 70144#0 Ki ni oruko bibi osere Ade Love 70154#0 Ebun fiimu wo ni Nse Ikpe-Etim gba ni odun 2014? 70169#0 Awọn orukọ wo ni a n pe ni orukọ amutorunwa? 70186#0 Ọdún wo ni Ayo Fayose di gomina ipinlẹ Èkìtì? 70298#0 Omo ilu wo ni Kemi Adeosun? 70317#0 Ọdún wo ni òṣèré Rachel Oniga bẹrẹ sí ṣe eré itage? 70430#0 Odun wo ni Stella Obasanjo s'alaisi? 70487#0 Omo meloo ni Bose Ogulu bi? 70501#0 ọdun wo ni Teniade Aofiyebi kopa ninu fiimu Flower Girl? 70508#0 Ara ilu wo ni Lisa Omorodion? 70580#0 oṣere wo ni a mọ si Hubert Ogunde? 70588#0 awon fiimu wo ni Rosaline Meurer ti se? 70604#0 Omo orile ede wo ni Kamaru Usman? 70639#0 Ile iṣe wo ni Ugonna Umerou da silẹ? 70723#0 Ọmọ orile ede wo ni Kansiime Anne? 70727#0 onkowe wo lo kọ Igbo olodumare? 70760#0 Ibasepo wo lo wa laarin Tariro ati Emmerson Mnangagwa? 70931#0 Kontinenti wo ni Peru wa ? 71075#0 Ta ni o kọkọ jẹ aare orile ede Tunisia? 71133#0 Orile ede wo ni Kunqu Opera ti wá? 71225#0 Orile-ede wo ni wọn bi Elon Musk si? 71253#0 Awon oṣere wo lo se ere Love Castle? 71290#0 Odun wo ni Nana Akufo Addo je aare orile ede Ghana? 71301#0 Odun wo ni Erica Nlewedim kopa ninu ere Big Brother? 71355#0 Orile ede wo ni Sacramento wa? 71373#0 Orile ede wo ni ilu Ghadames wa? 7147#0 Agbegbe wo ni Eko ni Desmond Elliot n se asoju fun? 7148#0 ọdun wo ni wọn bẹrẹ Ẹbun Nobel? 9149#0 Ki ni oluilu ipinle Ọsun? 9505#0 Odun wo ni wọn bi akọrin Adekunle Gold? 9593#0 Kí ni orúkọ bibi akọrin Naira Marley?